cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ní ìjọba ìbílẹ̀ òkè-ẹ̀rọ ẹ̀wẹ̀, wọ́n a máa sọ Ìgbómìnà ní ìdòfin..
wikipedia
yo
Ní ti ìjọba ìbílẹ̀ Isis, a rí ìlú bíi Òkè-Oni-gbìn-ín, òwú-Isis, èdìdì, ìjàrá, Ọwá Kájọlà, Ìru-Isis, ọlá àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Lóòótọ́, àwọn ìlú tí a dárúkọ bí ìlú tí a ti ń sọ ẹ̀ka-èdè Ìgbómìnà máa ń gbọ́ ara wọn ní àgbọ́yé bí wọ́n bá ń sọ̀rọ̀ síbẹ̀ oríṣiríṣi ní ẹ̀yà ẹ̀ka-èdè Ìgbómìnà tí wọ́n ń sọ láti ìlú kan sí èkejì..
wikipedia
yo
Ẹ̀KA-ÈDÈ ÌGBÓMÌNÀ Ọ̀RỌ̀ ṢÌ JẸ́ Ọ̀KAN LÁRA Ẹ̀YÀ Ẹ̀KA-ÈDÈ ÌGBÓMÌNÀ TÍ WỌ́N Ń SỌ NÍ Ẹkún Ọ̀RỌ̀..
wikipedia
yo
Odejobí (2004), ‘Àkọ́ ìgbékalẹ̀ ìwà ìwà ọ̀daràn nínú fiimu àgbéléwò Yorùbá'. Àpilẹ̀kọ fún Oyè Eè Ddélé, OAU, Ifẹ̀, Ìfẹ́.ÀṢAMỌ̀ Nigeria yìí ṣe àyẹ̀wò sí bí ìṣẹ̀lẹ̀ inú àwùjọ ṣe jẹ́ ọ̀pá ìwà ọ̀daràn nínú ìṣọwọ́ àwọn fiimu àgbéléwò Yorùbá kan, B.A..A..A..
wikipedia
yo
‘Ogun àjàyè', ‘Owo Blow', ‘Aṣẹ́wó Kano ‘Agbo Ọ̀dájú', ‘Haa', abbl..
wikipedia
yo
Àlàyé wáyé lórí ọ̀nà ìgbékalẹ̀ ọ̀ràn nínú fiimu àgbéléwò Yorùbá, bákan náà ni a sì tún ṣe àyẹ̀wò ipá tí fiimu àgbéléwò ajẹmọ́ ọ̀ràn dídá n ní lórí àwọn òǹwòran, òṣèré lọ́kùnrin-lóbìnrin àti àwùjọ lápapọ̀..
wikipedia
yo
Iṣẹ yìí ṣe àyẹ̀wò ohun tó n mu ki àwọn asefíìmù ó máa ṣe àgbéjáde fíìmù Yorùbá ajẹmọ́ ọ̀ràn dídá tó lu ìgboro pa báyìí, a sì tún wo oríṣiríṣi ìjìyà tí àwọn ọ̀daràn máa ń gbà..
wikipedia
yo
Tíọ́rì ìmọ̀ ìfojú ìbára-ẹni-gbépọ̀ ni a lò kí a le fi ọ̀ràn dídá inú fíìmù wé ti ojú ayé..
wikipedia
yo
Ìfọ̀rọ̀ wá àwọn àṣẹfíìmù lẹ́nu wò wáyé láti mọ ìdí tí wọ́n fi ń gbé fíìmù ajẹmọ́ ọ̀ràn dídá jáde..
wikipedia
yo
A tun fi ọ̀rọ̀ wá àṣàyàn àwọn oṣere lọkunrin ati lobinrin ati òǹwòran lẹ́nu wò lati mọ ìhà ti wọn kọ si fiimu ajẹmọ́ ọ̀ràn dídá àti ipa ti wíwọ irúfẹ́ fiimu bẹẹ le ni lori awọn eniyan ninu àwùjọ..
wikipedia
yo
Àwọn fíìmù àgbéléwò Yorùbá tó jẹ mọ́ iṣẹ́ yìí ni a wó tí a sì tú palẹ̀..
wikipedia
yo
olùwádìí tún lọ sí ilé ìkàwé láti ka ọ̀pọ̀ ìwé bíi Jona, Atiku, Ìwé Iṣẹ́ Abo-Ìwádìí láti lè mọ àwọn iṣẹ́ tó ti wà nílẹ̀..
wikipedia
yo
Iṣẹ́ ìwádìí yìí fi hàn pé ìyàgàn ati àìní tó jẹ mọ́ ọwọ́, ipò, obinrin ati àwọn nǹkan mìíràn ti ẹ̀dá lépa ló ń ti àwọn eniyan sinu ìwà ọ̀daràn..
wikipedia
yo
Iṣẹ́ yìí ṣe akiyesi pé lára àwọn tó ń lọ́wọ́ ninu ìwà ọ̀daràn ni a ti rí ọ̀rẹ́, ẹbí ati àwọn agbófinró..
wikipedia
yo
Bákan náà ni iṣẹ́ yìí tún ṣe àfihàn onírúurú ọ̀nà tí àwọn ọ̀daràn wọ̀nyí ń gbà dá ọ̀ràn..
wikipedia
yo
Iṣẹ́ yìí gbà pé àwọn ìwà ọ̀daràn tó ń ṣẹlẹ̀ ni a lè kà sí ọ̀kan lára ohun tí ìṣẹ̀lẹ̀ àwùjọ bí ati pé ìjìyà tí à ń fún ọ̀daràn máa ń ní ipa ninu ẹbí wọn nígbà mìíràn..
wikipedia
yo
Ilu irẹlẹ Akinyomade (2002), ‘Ilu Ipese', lati inu ’ipa obinrin ninu ọdun ẹjẹ ni Ilu Irele apileko fun oye biEE, Dall, OAU, Ife, Nigeria, oju-iwe 3-12.Àpèjúwe Ilu Ipese Irele je okan pataki ati eyi ti o tobi ju ninu ìkàlẹ̀ mẹsan-an (irẹlẹ, Àjàgbà, Omi, Idẹpe-Okitipupa, Aye, Ikọ̀ya, Ilu Tuntun, Kabedo ati ijùke, Èrìnjẹ̀, Gbòdì, Gbòdì-Dan Lisa)..
wikipedia
yo
Ìlú yìí wà ní ila-oorun gusu Yorùbá (Sey) gẹ́gẹ́ bí ìpínsí-ìsọ̀rí oyèlaran (1967), ó sì jẹ́ ibijókòó ìjọba ìbílẹ̀ ìrẹ̀lẹ̀..
wikipedia
yo
Ìlú yìí jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìlú tí ó ti wà ní ìgbà láéláé, àwọn olùgbé ìlú yìí yóò máa súnmọ́ ẹgbẹ̀rún lọ́nà ẹgbàá..
wikipedia
yo
Ní apá ìlà-oòrùn, wọ́n bá ìlú Anabomi ati igbótu pààlà, ní apá ìwọ̀-oòrùn ìlú ọ̀rẹ́ ati Odigbo pààlà, ní àríwá tí wọ́n sì bá ìlú Okitipupa-idẹpe ati Igbobini pààlà nígbà tí gúsù wọn bá ìlú omi pààlà..
wikipedia
yo
Ìrẹ̀lẹ̀ jẹ́ ìlú tí a tẹ̀dó sórí yanrìn, tí òjò sì máa ń rọ̀ ní àkókò rẹ̀ dáradára..
wikipedia
yo
Eléyìí ni ó jẹ́ kí àwọn olùgbé inú ìlú yìí yan iṣẹ́ àgbẹ̀ àti iṣẹ́ ẹja pípa ní ayọ̀ gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ òòjọ́ wọn ṣe wọ́n ni oko lérè Àgbẹ̀..
wikipedia
yo
Ohun tí wọ́n sábà máa ń gbìn ni òpè, obì tí ó lè máa mú owó wọlé fún wọn..
wikipedia
yo
Wọ́n tún máa ń gbin iṣu, ẹ̀gẹ́ kòkó, kukunìkọ́ àti ewébẹ̀ sínú oko àrojẹ wọn..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó Diláti ẹ ilẹ̀ wọn kò tó, tí ó sì tún ń ṣà, tí wọ́n sì ń pọ̀ sí i, àwọn mìíràn fi ìlú sílẹ̀ láti lọ mú oko ní ìlú mìíràn..
wikipedia
yo
Ìdí èyí ló fi jẹ́ pé àwọn ará ìlú yìí fi fi oko ṣe ilé ju ìlú wọn lọ..
wikipedia
yo
Lára oko wọn yìí ni a ti ri kidìmọ̀, litótó, líkanran, ọ̀fọ̀, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Ṣugbọn nígbà tí ọ̀làjú dé, àwọn ará ìlú yìí kò fi iṣẹ́ àgbẹ̀ ati ẹja pípá nìkan ṣe iṣẹ́ mọ́, àwọn náà ti ń ṣe iṣẹ́ ayàwòrán, télọ̀, bíríkìlà, awakọ̀, wọ́n sì ń dá iṣẹ́ sílẹ̀..
wikipedia
yo
Wọ́n ní ọjọ́ tí wọ́n máa ń kó èrè oko wọn lọ láti tà bíi ọjà Aráró, Ọjà Ọba, àti Ọjà Konye tí wọ́n máa ń kó èrè oko wọn lọ láti tà bíi Ọjà Aráromi, Ọjà Ọba, àti Ọjà Kòyẹ tí wọ́n máa ń ná ní Ọ̀rọ̀ síra wọn..
wikipedia
yo
Wọ́n máa ń bọ odò, ayélálá, aré-léron bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Wọ́n máa ń ṣe ọdún egungun, Ṣàngó, ogún, ọ̀rẹ́ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n nígbà tí ẹṣin àjòjì dé wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí ń yí padà láti inú ẹ̀sìn ìbílẹ̀ wọn sí ẹ̀sìn kúmumumi àti ẹṣin Kírísítẹ́nì..
wikipedia
yo
Oríṣìíríṣìí ohun àmúlúdún ni ó wà ní ìlú ìrẹ̀lẹ̀, bíi ina mona-mona, omi-ẹ̀rọ, ọ̀dà ojú pópó, ilé ìfowópamọ́, ilé ìfìwé-ránṣé, ilé-ìwé gíga àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.Ìtàn ìlú ìrẹ̀lẹ̀ ìrẹ̀lẹ̀ jẹ́ ọ̀kan pàtàkì nínú ilẹ̀ Yorùbá tí ḿ bẹ ní ìhà “Òndó Province” ó sì tún jẹ́ ọ̀kan kókó nínú àwọn ilé mẹ́ta pàtàkì tí ń bẹ ní “Okitipupa Division” tàbí tí a tún ń pè ní ìdàkejì gẹ́gẹ́ ẹsẹ̀ odò ti ọwọ́ òwúrọ̀ ilẹ̀ Yorùbá..
wikipedia
yo
Ìwádìí fi yé wa wí pé ọmọ ọba Benin tó jọba sí ìlú Ùgbò1 tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ olùgbọ́-ameto2 bí gbangba àti Aàjàa..
wikipedia
yo
Gbangba jẹ́ àbúrò àjànà ṣùgbọ́n nígbà tí olùgbọ́-ametọ wàjà, àwọn afọbajẹ gbìmọ̀pọ̀ láti fi gbangba jẹ́ ọba èyí mú kí Àid bínú kúrò ní ìlú, ó sì lọ tẹ ìlú _*lálọ́lá3 pẹ̀lú gbógun arákùnrin rẹ̀..
wikipedia
yo
Láti ìlú Hamubo ní ààjàa ti lọ sí ìlú Benin, ó sì rọ̀jò fún ọba Uforámì bí wọ́n ṣe fi àbúrò òun jọba, àti pé bí òun náà ṣe tẹ ibìkan dó..
wikipedia
yo
Ọba Uforámì si fun Aeto ni Ade, Aeto padà si Lokibo, o bi ọrunbumẹ́kùn ati Ogeyìnbó, ọkùnrin si ni àwọn méjèèjì..
wikipedia
yo
O duro si odo oba Benin pe baba oun ti wàjà, oun yoo si joba..
wikipedia
yo
ọ̀runbemẹ́kùn náà lọ sí ọ̀dọ̀ ìyá ọba Benin pé òun náà fẹ́ jọba nígbà tí baba òun ti kú..
wikipedia
yo
ỌBA BENIN Ń ṢE Ọ̀RỌ̀ ỌBA FÚN Ogeyìnbó NÍGBÀ TÍ ÌYÀ ỌBA Ń ṢE Ọ̀RỌ̀ FÚN Ọ̀RUNSUmẹ́kùn..
wikipedia
yo
Nígbà tí Àkọ́dá ọba Benin tí yóò wá gbé oúnjẹ fún ìyá ọba, rí i wí pé ọ̀rọ̀ tí ọba ń ṣe fún àlejò ọ̀dọ́ rẹ̀ náà ni ìyá ọba ń ṣe fún ẹni yìí..
wikipedia
yo
Èyí mú kí Àkọ́dá ọba fi ọ̀rọ̀ náà tó kabiyesi létí..
wikipedia
yo
Ní ọba ni ọmọ kì í bí ṣáájú ìyáa rẹ̀, ó pe Ibiyìnbó kó wá máa lọ..
wikipedia
yo
Nígbà tí àwọn méjèèjì fi lọ sí Benin, gbógunron ti gbé "Agba Madara"6 pamo nítorí ó ti fura pé wọ́n kò ní bá inú ìré̀n wa..
wikipedia
yo
Ibiyìnbó dé rọ́bó, kò rí àgbà málókun mọ́, ó wá gbé ufura, ó wọ inú ọkọ̀ ojú omi, ó sì tẹ ìsàlẹ̀ omi lọ, òun ni ó tẹ ìlú Èrìnjẹ̀ dó..
wikipedia
yo
Ní àkókò tí Ọrunbumẹ́kùn fi wà ní ìlú Benin, ọlọ́bibi, Ọmọ rẹ̀ máa lọ wẹ́ lọ́dọ̀ ipòba7 àwọn ẹru ọba sì maá n ja láti fẹ́ èyí ló fa ìpèdè yìí “Olobitan máa lọ wẹ́ jù kí ẹrú ọba méjì máa ba jijà kú tori ẹ̀"
wikipedia
yo
Oríṣìíríṣìí ogun ló jà wọ́n ní odi òhùmọ̀, lára wọn ni ogun Òṣokolo10, ogun UJọ11, ati bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Olùmisọkún ọmọ ọba Benin, iyawo rẹ̀ kò bímọ nígbà tó dé ìrẹ̀lẹ̀ ó pa àgọ́ sí ibìkan, ibẹ̀ ni wọ́n tí ń bọ̀ málókun ní ìlú ìrẹ̀lẹ̀..
wikipedia
yo
lúmù wa dó ní ìlú ìrẹ̀lẹ̀, ó fẹ́ ọlọbímítàn ṣùgbọ́n olóbímítàn kò bímọ fún un èyí mú kí ó padà wá sí ọ̀dọ̀ baba rẹ̀, ọ̀runbemẹ́kùn, olùroko wá fẹ́ ọlọbímí ní ọ̀dọ̀ òhùmọ̀..
wikipedia
yo
Wọ́n bí jàgbójú àti oyènusi, ogun tó jà wọ́n ní ni ọ̀dọ̀ óhùmọ̀ pa oyènusi èyí mú kí jagbójú sọ pé “Òun relé baba mi”..
wikipedia
yo
Àtè-olókùn ìwà òkun, òkun ni ẹyin òkun, òkun ni a kì í rídìí òkun a kìí rídìí ọlọ́ṣà ọmọ ìrẹ̀lẹ̀ kọ́ ni òpin ìdí ìgbàlẹ̀ kì í ọ̀sẹ̀ funfun tí málókun ọ̀pẹ ní tí málókùn” . Nǹkan èèwọ̀ fún ọmọ bíbí ìlú ìrẹ̀lẹ̀é òkété èrò koko ẹran àjà ẹ̀kowó ọ̀rọ̀ 1 Ùgbò Orúkọ ìlú kan ní ìlú Ìlàjẹ ni jẹ́ bẹ́ẹ̀..
wikipedia
yo
3 gbangba àti Aàjàa = Orúkọ Ènìyàn.4 Iroko = Ìlú kan ni je bee ni ipilẹ Ìlàjẹ 5 Ọba Uforámì = Orúkọ Ọba Benin..
wikipedia
yo
7 Àgbà Madara = Orúkọ ilu kan ni ti won n lu ni ojo odun Malọ́kùn..
wikipedia
yo
8 Ipòbá = Orúkọ Omi kan ní ìlú Benin9 Ùgbòtu = Orúkọ ìlú Àwọn Ìlàjẹ kan ni..
wikipedia
yo
11 Ogun Òṣokolo = Orúkọ ìlú kan tó kó ogun ja ìlú Irele..
wikipedia
yo
12 Ujo = Orúkọ àwọn ẹ̀yà ènìyàn kan níbo ìtọ́kasíYorùbá..
wikipedia
yo
bamijí ọjọ́ (20 October, 1939) jẹ́ Olùkọ̀wé ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà.Ìtàn ìgbésíayé bámijí ọjọ́a bí bámijí ọjọ́ ní ogúnjọ́ oṣù Kẹwàá ọdún 1939 ní ìlú Ìraarà, ní Ìjọba ìbílẹ̀ Afijio ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀jọ́..
wikipedia
yo
Oruko awon obi re ni Jacob Ojo ati Abimbola Àjọkẹ́ Ojo..
wikipedia
yo
Ojú ti ń là díẹ̀ nígbà náà, ẹni tí ó bá mú ọmọ lọ sí ilé-ìwé ní ìgbà náà, bí ìgbà tí ó fi ọmọ ṣọfà tí ó mú ọmọ lọ fún òyìnbó ni..
wikipedia
yo
Ṣugbọn àwọn òbí rẹ̀ pa ìmọ̀ pọ̀ wọ́n fi sí ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti Ìjọ Onítẹ̀bọmi ti First Baptist Day School ìlú Araaraa ní ọdún 1946..
wikipedia
yo
Ó se àsèyẹrí nínú ẹ̀kọ́ oníwèé mẹ́fà, tí ó kà jáde ní ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀..
wikipedia
yo
Nígbà náà wọ́n tí ń dá ilé ẹ̀kọ́ gíga mọdá (Modern School) sílẹ̀..
wikipedia
yo
bámijí Òjó ṣe ìdánwò bọ́ sí ilé-ìwé Local Authority Modern School ní ìlú Fìdítì, ó wà ní ibẹ̀ fún ọdún mẹ́ta (1956-1959)..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn èyí nínú ọdún 1960, Oyèbami ọjọ́ ṣe iṣẹ́ díẹ̀ láti fi kówó jọ..
wikipedia
yo
Nítorí pé kò sí owó lọ́wọ́ àwọn òbí rẹ̀ láti tò ó kọjá ìwé mẹjọ..
wikipedia
yo
Leyin ti o ti sise ti o si kerin jo fun odun kan pelu iwe eri "Modern School", o tun tiraka lati tesiwaju arun re re..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé-ìwé ti àwọn olùkọ́ni ti “Local Authority Teacher Training College” ní ìlú Ọ̀yọ́ láti inú ọdún 1961 di ọdún 1962..
wikipedia
yo
Ìgbà tí ó parí ẹ̀kọ́ rẹ̀ ni ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tíṣà, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé kì í ṣe iṣẹ́ tí ó wù ú lọ́kàn gan-an láti ilẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ní iṣẹ́ tíṣà..
wikipedia
yo
Ó ṣe iṣẹ́ tíṣà káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ bí i ṣákì, èdè, ahá..
wikipedia
yo
bamijí Òjó wà lára àwọn méjìlá àkọ́kọ́ tí wọ́n gbà ní ọdún 1969 láti kọ́ Yorùbá ní Yunifásítì Èkó..
wikipedia
yo
Nígbà náà ojú olè ni wọ́n fi máa ń wo ẹni tí ó bá lọ kọ́ Yorùbá ní yunifásítì..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí ó parí ẹ̀kọ́ rẹ̀ ni wọ́n gbà bámijí ọjọ́ sí ilé iṣẹ́ ìròyìn ní ọdún 1970, Alháàjí Lateef Jakande ni ó gbà á sí iṣẹ́ ìròyìn ní ilé-iṣẹ́ “Tribune”ní ìlú Èkó, gẹ́gẹ́ bí igbá kejì olóòtú Ìròyìn Yorùbá..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n nítorí pé ó tín í ìyàwó nílé nígbà náà wọ́n gbé e padà sí Ìbàdàn..
wikipedia
yo
Ní àsìkò yìí kan náà ni bámijí ọjọ́ ronú pé iṣẹ́ ìròyìn ti orí rédíò ṣáà ni ó wu òun..
wikipedia
yo
O wa n ba wọn sise AÁYAN ògbufọ̀ ni ile-ise "Radio Nigeria"
wikipedia
yo
Èyí ni ó ń ṣe tí ó fi ń ṣiṣẹ́ nílẹ̀ iṣẹ́ “Tribune” àti nílé isẹ́ “Radio Nigeria”
wikipedia
yo
Ni ọdun 1971 ni won gba bamiji Ojo gege bi onise iroyin ni ile ise "Radio Nigeria"
wikipedia
yo
Àwọn tí wọ́n jíjó ṣíṣe ìròyìn nígbà náà ni alàgbà ọ̀laolú olùmíìde tí ó jẹ́ ọ̀gá rẹ̀, olóògbé Alháàjí ṣáká ṣìkàgbọ́ àti olóògbé Akíntúnde Ògúnṣínà àti baba omidèyí..
wikipedia
yo
Nitori itara ọkan ti bamiji Ojo ni lati sise nile ise tẹfí o kuro ni "Radio Nigeria", o lo si "Western Nigerian BroadCastint Service" ati "Western Nigerian televeision Station" WNbs/WNTV to wa ni ago Ibadandi Ibadan, ninu osu Kọkànlá odun 1973..
wikipedia
yo
Ní ibẹ̀ ni ọkà rẹ ti balẹ̀ ti ayé sì ti gbà á láti lo ẹ̀bùn rẹ láti gbé èdè, àṣà àti lítíréṣọ̀ Yorùbá lárugẹ..
wikipedia
yo
Ìràwọ̀ rẹ̀ sì bẹ̀rẹ̀ sí i tàn gidigidi lẹ́nu iṣẹ́ ìròyìn..
wikipedia
yo
Nígbà tí ṣbáṣlẹ̀ Ojo wà ní "Radio Nigeria" kí ó tó lọ sí "Western Nigerian Television Station (WNTV)" ni wọ́n ti kọ́kọ́ ran àwọn onísẹ́ ibè lọ sí ilé ẹ̀kọ́ láti lọ kọ́ kọ ẹkọ́ bí wọ́n ṣe ń ṣiṣẹ́ ní iṣẹ́ iṣẹ́ redio..
wikipedia
yo
Ile ise redio ni Ikoyi ni wọn ti gba ìdánilẹ́kọ̀ọ́ yìí..
wikipedia
yo
Ìdí nipé ẹ tí ènìyàn bá máa sọ̀rọ̀ nílé iṣẹ́ “Radio Nigeria”Nígbà náà o gbọ́dọ̀ kọ́ ẹ̀kọ́..
wikipedia
yo
Lára àwọn ètò tó máa ń ṣe lórí ẹ̀rọ tẹlifíṣàn ní “Anti-oò-jíire” àti “Tiwa-n-tiwa” Túbọ̀ Ọládàpọ̀, Laoye Bedun àti àwọn mìíràn ni wọ́n jọ wà níbi iṣẹ́ nígbà náà..
wikipedia
yo
Gbogbo akitiyan yìí mú kí ìrírí àṣeso gbòòrò si nípa iṣẹ́ ìròyìn àti ìṣẹ̀lẹ̀ àwùjọ pẹ̀lú àwọn ènìyàn inú rẹ̀..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1976 ni bámijí Òjó lò fún ìdáni lẹ́kọ̀ọ́ ní òkè òkun, ní orílẹ̀ èdè Kenya níbi tí ó ti gba ìwé ẹ̀rí “Certificate course in Mass Communication” (Ìlànà ìgbétékalẹ̀ lórí afẹ́fẹ́)..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó di oṣù kẹwàá ọdún 1976, ni wọ́n dá àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́ta sílẹ̀, Ọ̀yọ́, Òǹdó àti ogun, bámijí jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tí ó kúrò ní ilé iṣẹ́ “Western Nigerian Broadcasting Services” àti “Western Nigerian Television Station (WNBS/WNTV) tí ó lọ dá Rédíò Oyo sílẹ̀..
wikipedia
yo
Ṣebíeer Olúwọlé Dare ni ó kó wọn lọ nígbà náà, Kúnlé Adélé, Adebayo ni wọ́n jíjó da ilé iṣẹ́ rédíò sì lé ní October 1976, wọ́n kọ́ ilé iṣẹ́ wọn lọ sí oríta Baṣọ̀run Ìbàdàn..
wikipedia
yo
Nínú ọdún 1981 ni bámijí ọjọ́ tún pa iṣẹ́ tì, tí ó tún lò fún ètò ìdánilẹ́kọ̀ọ́ lórí bí a ṣe ń ṣe iṣẹ́ rédíò ní ilé iṣé rédíò tí ó jẹ́ gbajúgbajà ní àgbáyé tí wọ́n ń pè ní “British Broadcasting Co-operation (BBC) London fun Certificate course..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1983 ni ó lọ sí orílẹ̀ èdè Germany fún ìdánilẹ́kọ̀ọ́ oloolorún mẹ́ta ní ilé iṣẹ́ rédíò tí à ń pè ní "Voice of Germany"
wikipedia
yo
Níbẹ̀ lo ti kọ́ ẹ̀kọ́ nípa iṣẹ́ rédíò àti móhùnhùn..
wikipedia
yo
Ìgbà tí bámijí ọjọ́ dé ni ó jókòó ti iṣẹ́ tí ó yìn láàyò..
wikipedia
yo
Èyí ni ó ń ṣe títí tí wọ́n tún fi pín Ọ̀yọ́ sí méjì tí àwọn osùn lọ, èyí mú kí àǹfààní wá láti tẹ̀ síwájú..
wikipedia
yo
Oríṣìíríṣìí ìgbéga ni ó wáyé nígbà náà ṣùgbọ́n ìgbéga tí ó gbẹ́yìn nínú iṣẹ́ oníròyìn ní “Director of programmes’ tí wọ́n fún bámijí ọjọ́ nínú oṣù kẹsàn-án, ọdún 1991, ó sì wà lẹ́nu iṣẹ́ náà gẹ́gẹ́ bí olùdarí àwọn ẹ̀ka tí ó ń gbóhùn sáfẹ́fẹ́ títí di ọdún 1994..
wikipedia
yo
Ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n oṣù kejìlá ọdún 1994 ni ó fẹ̀yìn tì..
wikipedia
yo
Ní ọdún tí ó tẹ̀lé, nínú oṣù kìíní ọdún 1995 ni bámijí ọjọ́ dá ilé iṣé tirẹ̀ náà sílẹ̀..
wikipedia
yo
Eyi ti o pa orúkọ rẹ ni 'Tunbami ọjọ communiwóCati Centeroṣù
wikipedia
yo
bámijí ọjọ́ tín í ìyàwó bẹ́ẹ̀ ni Ọlọrun sì ti fi ọmọ márùn-ún dá a lọ́lá..
wikipedia
yo