cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ní ọdún 1926 ni ẹgbẹ́ tí a mọ̀ sí “Ìjẹ̀bú - Jẹ̀ṣà Progressive Union” yí orúkọ ìlú náà kúrò láti Ìjẹ̀bú - Ẹrẹ̀ sí Ijẹ̀bú - Jẹ̀ṣà nítorí pé ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà ni Ìjẹ̀bú yìí wá..
wikipedia
yo
A níláti tọ́ka sí i pé Ìjẹ̀bú ti Ìjẹ̀ṣà yí lè ní nnkan kan í ṣe pẹ̀lú Ìjẹ̀bu ti Ìjẹ̀bù –Òde..
wikipedia
yo
Ìtàn lè pa wọ́n pọ̀ nípa àjọjẹ́ orúkọ, àjọṣe kankan lè má sí láàárin wọn nígbà kan ti rí ju wí pé orúkọ yìí, tó wu Ògbóni kìíní Ọba Ijẹ̀bú-Jẹ̀ṣà nígbà tí ó bá àbúrò rẹ̀ Ajíbógun lọ bòkun, wọ́n gba ọ̀nà Ìjẹ̀bú-Òde lọ..
wikipedia
yo
Ibẹ̀ ló gi mú orúkọ yìí bọ̀ tí ó sì fi sọ ìlú tí òun náà tẹ̀dó..
wikipedia
yo
Nínú àwọn ìtàn òkè yí àwọn méjì ló sọ bí a ṣe sọ ìlú náà ní Ijẹ̀bú ṣùgbọ́n ó dàbí ẹni pé a lè gba ti irúfẹ́ èyí tí ó sọ pé Ìjẹ̀bú - Òde ni Ọba Ijẹ̀bú Jẹ̀ṣà ti mú orúkọ náà wá ní eléyìí tí ó bójú mi díẹ̀..
wikipedia
yo
Orúkọ yìí ló wú n tí ó sì sọ ìlú tí òun náà tẹ̀dó ní orúkọ náà..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bí ìtàn àtẹnudẹ́nu, oríṣìíríṣìí ọ̀ná ni a máa ń gbà láti fi ìdí òótọ́ múlẹ̀, ṣùgbọ́n ó kù sọ́wọ́ àwọn onímọ̀ òde òní láti ṣe àgbéyẹ̀wò àwọn ìtàn wọ̀nyí kí a sì mú eléyìí tí ó bá fara jọ ọ̀ọ́tó jù lọ nínú wọn..
wikipedia
yo
Nípa pé tẹ̀gbọ́n tàbúrò ni Ọwá Iléṣà àti Ọba Ijẹ̀bú-Jẹ̀ṣà jẹ́ láti àárọ̀ ọjọ́ wa yìí, sọ wọ́n di kòrí – kòsùn ara wọn..
wikipedia
yo
Wọ́n sọ ọ́ di nnkan ìnira làti ya ara kódà, igbín àti ìkarahun ni wọ́n jẹ́ sí ara wọn..
wikipedia
yo
Ṣé bí ìgbín bá sì fà ìkarahun rẹ̀ a sẹ̀ lé e ni a máa ń gbọ́..
wikipedia
yo
ÌGBÀ tí ó di wí pé àwọn tẹ̀gbọ́n tàbúrò yí máa fi Ifẹ́ sílẹ̀, ìgbà kan náà ni wọ́n gbéra kúrò lọ́hùnún, apá ibì kan náà ni wọ́n sì gbà lọ láti lọ tẹ̀dó sí..
wikipedia
yo
Ọ̀rọ̀ wọn náà wá di ti ajá tí kì í lọ kí korokoro rẹ̀ gbélé..
wikipedia
yo
Àjọṣe ti ó wà láàárìn wọ́n pọ̀ gan-an tí ó fi jẹ́ wí pé ní gbogbo ìlẹ̀ Ijẹ̀ṣà, Ọba Ijẹ̀bú -Jẹ̀ṣà àti Ọwá Iléṣà jọ ní àwọn nnkán kan lápapọ̀ bẹ́ẹ̀ náà si ni àwọn ènìyàn wọn..
wikipedia
yo
Tí Ọwá bá fẹ́ fi ènìyàn bọrẹ̀ láyé àtijọ́, ọba Ijẹ̀bú-Jẹ̀ṣà gbọ́dọ̀ gbọ́ nípa rẹ̀..
wikipedia
yo
Tí Ọwá bá fẹ́ bọ̀gún, ó ní ipa tí Ọba Ijẹ̀bú-Jẹ̀ṣà gbọ́dọ̀ kó níbẹ̀, ó sì ní iye ọjọ́ tí ó gbọ́dọ̀ lò ní Iléṣà..
wikipedia
yo
Ní ọjọ́ àgùnlégún, ìlù ọba Ijẹ̀bú-Jẹ̀ṣà ni wọ́n máa n lù ní Iléṣa fún gbogbo àwọn àgbà Ìjẹ̀ṣà láti jó..
wikipedia
yo
Nígbà tí ọba ìgbà -Jẹ̀ṣà bá ń bọ̀ wálé lẹ́hìn ọ̀pọ̀ èè tí ó ti lọ ní Ileṣa fún ọdún ogun, ọtáforíjọfa ni àwọn èèyàn rẹ̀ ti gbọ́dọ̀ pàdé rẹ̀..
wikipedia
yo
Ìdí nìyí tí wọ́n fi máa ń sọ pé; “Káì bí an kọlijẹ̀bú níbi an tọ̀nà Ìjẹ̀ṣáá bo ọtájaja ọ̀nà ni an kọlijẹ̀bú Ọmọgbùrùkò èroko oyè ni wọ́n máa ń jẹ ni ilérin tí wọ́n sì ń jẹ ní Ìjẹ̀bú Jẹ̀ṣà a rí Ògbóni ní Iléṣà bẹ́ẹ̀ náà ni ó wà ní Ìjẹ̀bú Jẹ̀ṣà..
wikipedia
yo
Ara Ìwàrẹ̀fà mẹfà ni Ògbóni méjèèjì yí a ní Iléṣà ṣùgbọ́n ògbóni Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà ni aṣáájú àwọn Ìwàrẹ̀fà náà..
wikipedia
yo
A rí àwọn olóyè bí Ọbaálá, Rísàwẹ́, Ọ̀dọlé, Léjòfi Sàlóro Àrápatẹ́ àti Ọbádò ni Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà bí wọ́n ti wà ní Iléṣà..
wikipedia
yo
Bákan náà, oríṣìíríṣìí àdúgbò ni a rí tí orúkọ wọn bá ara wọn mu ni àwọn ìlú méjéèjì yí fún àpẹẹrẹ bí a ṣe rí ọgbọ̀n Ìlọ́rọ̀ ni Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà náà ni a rí i ní Iléṣà, Ọ̀kè wà ní Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà, Òkèsa sì wà ní Iléṣà..
wikipedia
yo
Odò-ẹsẹ̀ wà ní ìlú jèèjì yí bẹ́ẹ̀ náà ni Ẹrẹ́jà pẹ́lù..
wikipedia
yo
Nínú gbogbo àwọn ìlú tí ó wà ní ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà, adé tàbí ohun tí Iléṣà àti ti Ijẹ̀bú-Jẹ̀ṣà ló bá ara wọn mu jù lọ..
wikipedia
yo
Ọba Ijẹ̀bú-Jẹ̀ṣà ló máa ń fi Ọwá tuntun han gbogbo Ìjẹ̀ṣà gẹ́gẹ́ bí olórí wọn tuntun lẹ́hìn tí ó bá ti ṣúre fún un tán..
wikipedia
yo
Tí ọ̀kan nínú wọn bá sì wàjà, ón ní ogún ti wọ́n máa ń jẹ lọ́dọ̀ ara wọn bí aya, ẹrú àti ẹrù.Ní ìgbà ayé ògún, ọ̀tún ògún, ni Ijẹ̀bú-Jẹ̀ṣà jẹ́ ni ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà, wọ́n sì ní ọ̀nà tiwọn yàtọ̀ sí ti àwọn yòókù..
wikipedia
yo
Nígbà tí ilẹ̀ Iléṣà dàrú nígbà kan láyé ọjọ́un, ẹlòmíràn-kùnrin Ọwá àti ẹlòmíràn-bìnrin Ọba Ijẹ̀bú-Jẹ̀ṣà ni wọ́n fi ṣe ètùtù kí ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà tó rójù ráyè, kí ó tó tùbà tùṣẹ..
wikipedia
yo
Nítorí pé Ọba Ijẹ̀bú -Jẹ̀ṣà àti Ọwá Iléṣà jẹ́ tẹ̀gbọ́n tàbúrò látàárọ̀ ọjọ́ wa, àjọṣe tiwọn tún lé ìgbà kan ju ti gbogbo àwọn Ọba ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà tó kù lọ nítorí pé “Ọwá àti Ògbóni Ìjẹ̀bù -Jẹ̀ṣà ló mọ ohun tí wọ́n jọ dì sẹ́rù ara wọn”Ìwó ṣókí lórí ìlú àti àwọn ènìyàn Ijẹ̀bú-Jẹ̀ṣà Ìjẹ̀bú - Jẹ̀ṣà jẹ́ ìlú kan pàtàkì ní ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà..
wikipedia
yo
Apá ìwọ̀ oòrùn ni ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà wà ní ilẹ̀ Yorùbá tàbí àkókà - oò- jíire..
wikipedia
yo
Ìlú Ilẹ́ṣà ti ó jẹ́ olú ìlú fun gbogbo ilẹ̀ jẹ̀ṣà jẹ́ nnkan ibùsọ̀ mẹ́rìnléláàádọ́rin sí ìlú Ìbàdàn tí jẹ́ olú ìlú ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́..
wikipedia
yo
Ìlú Ijẹ̀bú - Jẹ̀ṣà sì tó nnkan bí ibùsọ̀ mẹ́fà sí Iléṣà ní apá àríwá ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà.Ní títóbi, ìlú Ìjẹ̀bú - Jẹ̀ṣà ni ó pọwọ́lé ìlú Iléṣà ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà, òun sì ni olú ìlú fún ìjọba ìbílẹ̀ Obòkun òun kí wọ́n tó tún un pín sí ọ̀nà mẹ́rin; síbẹ̀ náà òun ni olú ìlú fún ìjọba ìbílẹ̀ ààrin gùngùn Obòkun.Àdúgbò márùnún pàtàkì ni wọ́n pín ìlú yìí sí kì bá lè rọrùn fún ètò ìjọba ṣíṣe àti fúniṣẹ́ Ìlọ́rọ̀, Ọ̀kènísàkè àti Òdògo..
wikipedia
yo
Ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn àdúgbò yí ló ní Olórí ọmọ tàbí lóógun kọ̀ọ̀kan tí ó jẹ́ aṣáájú fún ọmọ àdúgbò rẹ̀ òun ní aṣáájú fún iṣẹ́kíṣẹ́ àti tí ó bá délẹ̀ láti ṣe ní àdúgbó, bẹ́ẹ̀ ni, ó sì tún jẹ́ aṣojú ọba fún àwọn ọmọ àdúgbò rẹ̀..
wikipedia
yo
Òdògo nìkan ni kò fi ara mọ́ èlò yí tó bẹ́ẹ̀ nítorí ìtàn tó bí i fi hàn pé ìlú ọ̀tọ̀ gédégédé ni òun..
wikipedia
yo
Àwọn ènìyàn ọ̀gbọ́n náà ń fẹ́ máa hùwà gẹ́gẹ́ bí ìtàn ìgbà ìwáṣẹ̀ ti fi hàn wí pé wọn kò ní nǹkan kan í ṣe pẹ̀lú Ìjẹ̀bú Jẹ̀ṣà..
wikipedia
yo
Lóde òní, nǹkan ti ń yàtọ̀ díẹ̀díẹ̀ nítorí pé àjọṣe tí ó péye ti ń wáyé láàárín ọ̀gbọ́n náà àti àwọn ọ̀gbọ́n yòókù.Ẹ̀rí tí ó fi hàn gbegbe pé àwọn Ìjẹ̀ṣà gba ìlú Ijẹ̀bú - Jẹ̀ṣà gẹ́gẹ́ bí ìlú tí ó tẹ̀ lé Iléṣà ní ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà ni pé ìjókòó àwọn lọ́balọ́ba ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà, Ọwá ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà ni ọba Ijẹ̀bú - Jẹ̀ṣà máa ń yàn án lé..
wikipedia
yo
Síwájú sí i, nípa ti ìlànà oyè jíjẹ, ó ní iye ọjọ́ tí Ọwá tuntun gbọ́dọ̀ lò ní Ijẹ̀bù - Jẹ̀ṣà láyé ọjọ́un..
wikipedia
yo
Ọba Ijẹ̀bú - Jẹ̀ṣà ni ó máa ń gbé Ọwá lésẹ̀ tí ó sì máa ń ṣúre fún un kí wọ́n tó gbà á gẹ́gẹ́ bí Ọwá àti olóri gbogbo ọba ilẹ̀ Ijẹ̀ṣà.Láti túnbọ̀ fi pátákí ìlú Ijẹ̀bú -Jẹ̀ṣà hàn, gẹ́gẹ́ bí ó ti wà nínú ìtàn ìwásẹ̀, tí Ọwá bá fẹ́ ṣe ìdájọ́ fún ọ̀daràn apànìyàn kan, Ọba Ijẹ̀bú - Jẹ̀ṣà gbọ́dọ̀ wà níjòkó, bí èyí kò bá rí bẹ́ẹ̀, Ọwá gbódọ̀ sùn irú igbẹ́jọ́ tàbí ìdájọ́ bẹ́ẹ̀ sí ọjọ́ iwájú..
wikipedia
yo
Ìdí nìyí tí wọ́n ṣe máa ń sọ pé“Ọwa ràà dáni í paná Ìjẹ̀bù -Jẹ̀ṣà mọ̀ mońkọ́wá bá a pani-Ìjẹ̀bú - Jẹ̀ṣà a gbọ́”iṣẹ́ àgbẹ̀ ní iṣẹ́ pàtàkì jùlọ tí àwọn ènìyàn ìlú Ijẹ̀bú - Jẹ̀ṣà ń ṣe..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ wọn ni ó jẹ́ àgbẹ̀ alárojẹ, bẹ́ẹ̀ ni a tún rí àwọn tó mú àgbẹ̀ àrojẹ mọ́ àgbẹ̀ agbinrúgbìn tó ń mówó wọlé lọ́dọ́ọdún àti láti ìgbàdégbà..
wikipedia
yo
Àwọn irúgbìn tí wọn ń gbìn fún àrojẹ ni, iṣu, ẹ̀gẹ́ (gbáàgúdá) ikókó, ìrẹsì, àgbàdo, kọfí, òwú àti obì sì jẹ́ àwọn irù-gbin tó ń mówó wálé fún wọn.A rí àwọn oníṣẹ́-ọwọ́ bíi, alágbẹ̀dẹ, onílù..
wikipedia
yo
Àwọn obìnrin wọn náà a máa ṣe oríṣìíríṣìí iṣẹ́-ọwọ́, lára wọn ni aró dídá, apẹ àti ìkòkò mímọ́ àti aṣọ híhun pẹ̀lú.Bákan náà, wọ́n tún jẹ́ oníṣòwò gidi..
wikipedia
yo
Ọmọ ìyá ni ẹlẹ́dẹ̀ àti ìmọ̀dò, bẹ́ẹ̀ náà sì ni inàki àti ọ̀bọ, gbogbo ibi tí a bá ti dárúkọ Ìjẹ̀ṣà ni a á ti máa fi ojú oníṣòwo gidi wò wọ́n..
wikipedia
yo
Elèyìí ni a fi ń pè wọ́n ní “Òṣómàáló” nítorí kò sí ibi tí a kó ti lè rí Ìjẹ̀ṣà ti ọ̀rọ̀ ìṣòwò bá délẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni kò sí irúfẹ́ owo tí wọn kò lè ṣe, ohun tí ó kó wọn ní irìnra ni ọ̀lẹ àti ọ̀lẹ..
wikipedia
yo
“alapa ma sise” ni awon Ìjèṣà máa ń pe àwọn ti kò bá lè ṣiṣẹ́ gidi..
wikipedia
yo
Ìjẹ̀ṣà kò kọ̀ láti kó ọmọ wọn lọ́mọ tí ó bá jalè tàbí tí kò níṣẹ́ kan pàtàkì lọ́wọ́..
wikipedia
yo
Wọn a si maa fi ọmọ wọn ti o ba jẹ akíkanjú tàbí alágbára yangàn láwùjọ..
wikipedia
yo
“Òkóbó nìkan ni kìí bímọ sí tòsí, a ní ọmọ òun wà ní òkè-òkun” bákan náà ni pé “arúgbó nìkan ni ó lè parọ́ tí a kò lè já a nítorí pé àwọn ẹgbẹ́ rẹ̀ ti kú tán” purọ́ n níyì, ẹ̀tẹ́ ní ń mú wá, bí irọ́ ni, bí òótọ́ ni pé àwọn Ìjẹ̀ṣà jẹ́ akíkanjú, ẹ wo jagunjagun ògèdèǹgbé “Agbógungbórò” Ọ̀gbó àgùnsóyè, “Ologun abẹ́ggọ̀, ó fònfòn tán, ó wojú ìwó kọ̀rọ̀, Ọ̀dọ̀fin Arówóbùbù, ògbókọ̀kò lérí lérí kí bí ígbọ́n sẹ́yìn sẹ́yìn” ológun arimọ́ àti àwọn Olórúkọ ńláńlá ni ilẹ̀ Ijẹ̀ṣà láyé ọjọ́un..
wikipedia
yo
Tí a bá tún wo àwọn oníṣòwò ńláńlá lóde òní nílẹ̀ Yorùbá jákèjádò, “Ọkan ni ṣànpọ̀nná kó láwùjọ èpè” ni ọ̀rọ̀ ti Ìjẹ̀ṣà..
wikipedia
yo
Nínú wọn ni a ti rí Àjànàkú, Erinmi lókun, Ọmọ́le Àmúùgbangba bíu ẹkùn, S.B..
wikipedia
yo
Bákà Olóye méjì lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo àti Onìbọnòjé àtàri àjànà tí kì í ṣẹrù ọmọdé..
wikipedia
yo
Mé lówù la ó kà lẹ́hìn Adépèlé ni ọ̀rọ̀ wọn.Àwọn ọmọ Ijẹ̀bú -Jẹ̀ṣà jẹ́ aláfẹ́ púpọ̀ pàápàá nígbà tí ọwọ́ wọn bá dilẹ̀..
wikipedia
yo
Àwọn ènìyàn tí ó fẹ́ràn àlàáfíà, ìfẹ́ àti ìrẹ́pọ̀ láàárin onílé àti àlejò sì ni wọ́n pẹ̀lú..
wikipedia
yo
Wọn máa ń pín ara wọn sí ẹlẹ́gbẹ́jẹgbẹ́ láti ṣe iṣẹ́ ìlú láti jọ kẹ́gbẹ́ àjùmọ̀ṣe lẹ́nu iṣẹ́ àti oríṣìíríṣìí ayẹyẹ nílùú pẹ̀lú..
wikipedia
yo
“ajẹjẹ ọwọ́ kan kò gbẹ́rù dórí” àjùmọ̀ṣẹ́ wọn yìí mú ìlọsíwájú wá fún ìlú náà lọ́pọ̀lọpọ̀ “Abiyamọ kì í gbọ́ ẹkún ọmọ rẹ̀ kó má tátì wèrè” ní ti àwọn ọmọ Ijẹ̀bú - Jẹ̀ṣà sí ohunkóhun tí wọ́n bá gbọ́ nípa ìlú wọn..
wikipedia
yo
Bí ọ̀rọ̀ kan bá délẹ̀ nípa iṣẹ́ ìlú, wọn máa ń rúnpá-rúnsẹ̀ sí i, wọ́n á sì mú sòkòtò wọn wọ̀ láti yanjú irú ọ̀rọ̀ náà..
wikipedia
yo
Ọmọ ọkọ ni àwọn ọmọ ìlú Ijẹ̀bú - Jẹ̀ṣà ní tòótọ̀.Síwájú sí i, oríṣìíríṣìí ọ̀nà tí ó bá òde òní mu ni wọ́n ti là sí ààrin ìlú láìní ọwọ́ ìjọba kankan nínú fún ìdàgbàsókè àti ìlọsíwájú ìlú wọn..
wikipedia
yo
Fún àpẹẹrẹ Ilé - Ẹ̀kọ́ gíga (Grammar Schoo) méji ti ó wà ni ilú náà, òógùn ojú wọn ni wọ́n fi kọ́ wọn, bẹ́ẹ̀ náà ni Modern School wọn..
wikipedia
yo
àrỌwỌbuisoye (1982), 'itan isedale ilu Ijebu-Jẹ̀ṣà' Dall, OAU, Ife, Nigeria.Ìpínlẹ̀ Osun..
wikipedia
yo
Kò sí èyí tó sọ pàtó ìgbà tàbí àkókò tí a dá ìlú Difọ̀-alààyè sílẹ̀..
wikipedia
yo
Púpọ̀ nínú ìtàn yìí ló máa ń rújú pàápàá tó bá jẹ́ ìtàn ìtẹ̀lúdò ní ilẹ̀ Yorùbá..
wikipedia
yo
Nítorí àìkò sílẹ̀ ìtàn yìí, kò jẹ́ kí a rí àkọsílẹ̀ gidi fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìlú ní ilẹ̀ Yorùbá nínú ibi tí ìlú ẹ̀fọn-alààyè ti jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ìlú bẹ́ẹ̀..
wikipedia
yo
Oríṣìí òpìtàn ni a rí, ìtàn wọn máa ń yàtọ̀ sí ara wọn, bí kò ní àfikún yóò ní àyọkúrò ọ̀kan pàtàkì lára ohun tí àwọn òpìtàn ti ṣiṣẹ́ lé lórí nípa ìtàn ilẹ̀ Afírika ni ìyànjú wọn láti wo ìtàn ìwáṣẹ̀, kí wọ́n tó lè fa òótọ́ yọ jáde..
wikipedia
yo
Ṣàṣà ni onímọ̀ kan tó ṣiṣẹ́ lórí ìtàn ìlú kan tàbí àdúgbò kan tí kò mú ìlànà ìtàn ìwáṣẹ̀ lọ láti ṣàlàyé tó bójúmu nípa orírun ìlú kan (Johnson 1921;3).Gẹ́gẹ́ bí àwọn òpìtàn ilẹ̀ Yorùbá, awọ òpìtàn ìlú ẹ̀fọn alààyè gbà pé odò Odùduwà ni wọ́n ti ṣe wá láti Ilé-Ifẹ̀..
wikipedia
yo
Lára àwọn òpìtàn yìí tilẹ̀ lérò pé ẹni tó tẹ ìlú ẹ̀fọn-alààyè dó rọ́ láti ojú ọ̀run sílẹ̀ ayé..
wikipedia
yo
Ìlú tó sọ̀kalẹ̀ sì ní ilé-Ifẹ̀ tó jẹ́ orírun àwọn Yorùbá..
wikipedia
yo
ìtàn yìí ṣòro láti gbàgbọ́, nítorí kò rí ìdí múlẹ̀..
wikipedia
yo
Nínú ìtàn ìwáṣẹ̀, òrìṣà àti Odù mẹ́rìndínlógún ni a gbọ́ pé wọ́n rọ̀ láti ípàdé wa sí iṣsalaye (Abimbola, W..
wikipedia
yo
Àwọn òpìtàn yìí lè rò pé bóyá nítorí tí a ti ń pe àwọn ọba ilẹ̀ Yorùbá ní igbákejì òrìṣà ni àwọn náà ṣe rò pé alààyè àkọ́kọ́ rọ̀ sílẹ̀ ayé láti ọ̀run.’Ọmọ Ọwá, ọmọ ẹkùnọmọ òkiriKíṣì ó tọ́jú ọ̀run á yẹ'nínú ìtàn ìwáṣẹ̀ mìíràn, a gbọ́ pé Ọbalúfọ̀n alaye ni ọba àkọ́kọ́ tí ó tẹ ìlú ẹ̀fọn-alààyè dó..
wikipedia
yo
Ọbalùfọ̀n Aláyémore yìí jẹ́ ọmọ Ọbalùfọ̀n Ògbòlélé tí í ṣe àkọ́bí Odùduwà tí ó jẹ́ Ọọ̀ni ti Ilé-Ifẹ̀ ní àkókò ìgbà kan..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ikú rẹ̀, Ọ̀rànmíyàn ló yẹ kí ó jẹ ọba ni Ilé-Ifẹ̀ ṣùgbọ́n ó tí lọ sílùú àwọn ọmọ rẹ̀, Eweka ni ẹìní àti Aláàfin ni Oyo..
wikipedia
yo
Ọbalùfọ̀n Aláyémore ti jẹ́ oyè Ooni kí okélọ́ tó dé.Nigba tí okélọ́ dé,more sá sá kúrò lórí oyè nítorí pé ní ayé àtijọ́ wọn kí i fi ẹni ìrán sílẹ̀ lati fi àrò joyé..
wikipedia
yo
Èyí ni ọba tó tẹ̀dó sórí òkè ṣùgbọ́n lónìí ọbaké ni wọ́n ń pe ibẹ̀.Ní orí òkè yìí, Ọbalúfọ̀n ṣe àkíyèsí pé ẹranko búburú pọ̀ ní agbègbè tó tẹ̀dó sí, èyí tó pọ̀jù ní ẹfọ̀n..
wikipedia
yo
Àwọn ẹfọ̀n kékeré níbẹ̀ ni wọ́n kójọ sínú ọgbà, tí wọ́n so wọ́n mọ́lẹ̀ títí wọ́n fi kú..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó ṣe Ọbalúfọ̀n alayemore ranse sí Ọ̀rànmíyàn kí ó fi nǹkan ìtẹludò ṣọwọ́ sí òun..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí wọ́n ti fi nǹkan yìí ránṣẹ́ sí Ọbalúfọ̀n alayemore; kò pé tí Ọ̀rànmíyàn kú..
wikipedia
yo
Àwọn ará Ilé-Ifẹ̀ wá ranṣẹ sí Ọbalùfọ̀n Asese láti wá jọba lẹẹkeji..
wikipedia
yo
Iyawo mẹta ni alayemore ni ki o to kuro ni ẹ̀fọn-alààyẹ̀..
wikipedia
yo
Àwọn ni adudu ọ̀ránkú tí í ṣe ìran àwọn Obologun; àpárápara ọrùn ìran àwọn aṣemọmọ, ẹ̀ẹ̀kẹ́ta ni Èṣù-gbé-ojú-ọ̀run-sàga-ìjà..
wikipedia
yo
Ìtàn sọ pé lásìkò tí Ọbalùfọ̀n ìmore padà sí Ilé-Ifẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Ọọ̀ni, bọ́ sí àkókò tí ọba Dàda Aláàfin Ọ̀yọ́ wà lórí oyè ní nǹkan bí 1200-1300ad.Bí ìtàn ìwáṣẹ̀ yìí ìbá ṣe rọrùn tó láti gbàgbọ́ àwọn askíyèsí kan ni a rí tọ́ka sí tí ó jẹ́ kí ìtàn náà rú ènìyàn lójú..
wikipedia
yo
Nínú ìtàn yìí, wọ́n sọ pé Ọbalùfọ̀n Ògbòlélé ni àkọ́bí Odùduwà, èyí tó tako ìtàn tí a ti mọ̀ tẹ́lẹ̀ nípa Odùduwà..
wikipedia
yo
Bó bá tilẹ̀ ṣe orúkọ ló yípadà, àwọn ọmọ ọ̀kanbí ní Ọba méje pàtàkì ní ilẹ̀ Yorùbá ti kọ́ sí Ọbalùfọ̀n nínú wọn..
wikipedia
yo
Ohun tí òpìtàn ìba sọ fún wa nip é ìran Odùduwà ní Ọbalúfọ̀n jẹ́.Àkókò tí ìṣẹ̀lẹ̀ yìí ṣẹ̀ rú ni lójú púpọ̀..
wikipedia
yo
Nínú ìtàn yìí a rí i pé Ọbalùfọ̀n alayemore mọ àsìkò tí Ọ̀rànmíyàn wà láyé..
wikipedia
yo
Lóòótọ́ ni Ọ̀rànmíyàn jẹ Ọba ní oko, tó tún wá sí Ilé-Ifẹ̀..
wikipedia
yo
aláàfin Dàda tí òpìtàn fẹnu bá pé ó jẹ ọba ní Ọ̀yọ́ da ìtàn rú..
wikipedia
yo
Tó bá jẹ́ òtítọ́ ni Ọbalùfọ̀n Aláyémore tún wá jọba lẹ́ẹ̀kejì ní Ilé-Ifẹ̀ a jẹ́ pé àsìkò Aláàfin Ajáka jẹ Ọba.Àwọn òtítọ́ kọ̀ọ̀kan farahàn nínú ìtàn yìí..
wikipedia
yo
Nínú ìtàn mìíràn, a gbọ́ pé àwọn oríṣìí ènìyàn bí i mẹ́fà ni wọ́n tẹ̀dó lásìkò ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ sí ẹ̀fọn-alààyè..
wikipedia
yo
Nínú ìtàn yìí, a gbọ́ pé ekuwí ló kọ́kọ́ dé sílùú ẹfọ̀n-alààyè, igbo-aba ni ekuwí tẹ̀dó sí..
wikipedia
yo
Òde kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Oríkìn náà tẹ̀dó sí igbó ààyè..
wikipedia
yo
Lọ́jọ́ kan, lásìkò tí oríkin tẹ̀dó, ó rí iná tó ń rú ní igbo-abà..
wikipedia
yo
Oríkìn rọ àwọn tó wà ní igbó abà kí wọ́n jọ má gbé ní Igbó-Ààyè..
wikipedia
yo
Igbakeji Ọbalùfọ̀n ti won jo wa lati Ile-Ife ni won fi je igbakeji oba ti a mo si Obanla..
wikipedia
yo
Bàbá Igbó Àbá ọjọ́sí ni wọ́n fi jẹ́ bàbá ọlọ́jà tí a mọ̀ sí Ọbalọ́jà..
wikipedia
yo
Ọbalùfọ̀n àti Ọbálọ́jà jẹ́ ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́ nígbà náà..
wikipedia
yo
BÍ ỌBA ṢE ń pàṢẸ FÚN ààyè ní ọbaLago ṣe ń pàṣé ní Ọbalú LÁYÉ ìgbà náà..
wikipedia
yo
Bí ọba kan bá wàjà ní ìlú Efọ́n-Alààyè, iwájú ilé ọba-ọlọ́jà ni wọn yóò kó ọjà lọ.Nínú ìtàn mìíràn a gbọ́ pé Ààfin Odùduwà ni wọ́n bí aláàyè sí..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ arẹwà ọkùnrin tí ènìyàn púpọ̀ fẹ́ràn rẹ̀ pàápàá àwọn babaláwo tó ń wá sí ààfin..
wikipedia
yo
Ìtàn yìí tẹ̀síwájú pé ọkùnrin yìí ní aáwọ̀ ní ààfin, èyí ló mú kí Odùduwà ṣe fún alààyè ní ilẹ̀ sí iraye tí a mọ̀ sí mọdákétì lónìí..
wikipedia
yo
Ninu itẹsiwaju, itan miiran to fara jọ itan oke yii, a gbọ pe awọn Ọmọọba meji lo fẹ lọ tẹ ilu do..
wikipedia
yo
Bó bá rí bẹ́ẹ̀ a jẹ́ pé ìlú ẹ̀fọn ti wà kí mọdákẹ̀kẹ́ tó dáyé..
wikipedia
yo
Atada àti Johnson tilẹ̀ máa ń to are àti ẹfọ̀n tẹ̀lé ara wọn.Ní pàtàkì, ogun kò ṣẹ́gun ẹ̀fọ́ alààyè rí àyàfi ogun ọdẹrinlọ (1852-54)..
wikipedia
yo