cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ó tún tẹ̀síwájú lọ sí Yunifásítì ti Ìbàdàn níbí tí ó ti gba oyè ẹ̀ka Ajémọ́ṣẹ́ Ọ̀nà (Bachelor of Arts) nínú èdè Gẹ̀ẹ́sì ní ọdún 1974, ọdún yìí náàni ó lọ ṣe ìsìn ìlú gẹ́gẹ́ bí Aguni ní ọdún 1975..
wikipedia
yo
Ọdún yìí ló darapọ̀ mọ́ Àjọ Aráàlú ti Ìwọ̀ Oòrùn Nàìjíríà (Western State Public Commission) gẹ́gẹ́ bi òṣìṣẹ́ ètò Èkó kí ó tó wá di olùkọ́ Èdè gẹ̀ẹ́sì ní Ibùdó Rákáràkátà ti ìjọba Government Trade Centre, Ìpínlẹ̀ Oyo..
wikipedia
yo
Ó gba oyè Master’s ní èdè Gẹ̀ẹ́sì, ọdún yìí lánàá ló darapọ̀ mọ́ kọ́lẹ́jì ẹ̀kọ́ṣẹ́ àwọn olùkọ́ni ti ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ gẹ́gẹ́ bí olùkọ́ tí wọ́n sì gbé e lọ sí Polytechnic ti Ìbàdàn níbi tí ó ti ga dé ipò igbákejì Olórí láàrin ọdún 1999 àti 2003 lẹ́yìn tí ó ti gba oyè onímọ̀ ìjìnlẹ̀ ẹ̀ro – (Ph.D) nínú lítíréṣọ̀ àti Gẹ̀ẹ́sì ní Yunifásítì Ìlọrin ní ọdún 1997.Orúkọ iṣẹ́iṣẹ́ rẹ̀ iṣẹ́..
wikipedia
yo
O ti gbé ogunlọ́gọ̀ ìwé jáde, àwọn ìtàn kéékèèké àti àwọn ìtàn àròsọ gẹ́gẹ́ bí ògbóǹtarìgì on..
wikipedia
yo
Wọ́n fi ìwé rẹ̀ àkọ́kọ́ “The Virgin”, ṣe fiimu orilẹede Naijiria meji..
wikipedia
yo
The Narrow Path, fiimu orilẹede Naijiria ti Tunde Kelani ṣe olóolo ti o si dari rẹ ni ọdun 2006, ṣe afihan Sola Aikude, ati The White Handker..
wikipedia
yo
Òun ló kọ́ lonely days, ìwé tí ó fọ́júsun àṣà ilẹ̀ Adúláwọ̀..
wikipedia
yo
Ó kó ipa pàtàkì nínú LÍTÍRÉṢỌ̀ Ajeko Adu ní GẸ̀Ẹ́SÌ..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1972, ìtàn rẹ̀ kékeré tí ó pè ní The River goddess gba àmì ẹ̀yẹ Western Festival of Arts Literary Competition..
wikipedia
yo
Bákan náà ni ọdún 1992, ewì rẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ ń perpàṣípààrọ̀ gba àmì ẹ̀yẹ Africa Prize nínú Index lórí Ìdíje Censọ8C International Poetry ní ìlú London..
wikipedia
yo
Wọ́n ti lo àwọn iṣẹ́ ninu iṣẹ́ ìwádìí bákan náà, wọ́n fi ń kẹ́kọ̀ọ́ ní ọpọlọpọ Yunifásítì.Àwọn ìtọ́ka sí “artistic Bells in a Science World”
wikipedia
yo
Archived from the original on 2015-04-10."The man who grew larger than life"
wikipedia
yo
Retrieved 2020-05-27."Welcome to Adeyípo village - Nigeria content Online"
wikipedia
yo
"How Syw is promoting unknown young Writers in Nigeria"
wikipedia
yo
Archived from the original on 2015-04-10."bearing witness"
wikipedia
yo
google.co.uk"Báyọ̀ adébọ̀wálé's Moving Lines for African Heroes"
wikipedia
yo
2006."Black African Literature in English, 1997-1999"
wikipedia
yo
Retrieved 2020-05-27.Ìtọ́kasíàwọn Olukọwe ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
rẹmi Àdùkẹ́ Adedeji tí a bi ni ọdun 1937 jẹ onkọwe oje-wẹ́wẹ́ ọmọ orilẹ-ede Naijiria.igbesi aye Adedeji jẹ ọmọ bibi Ilu Okemesi ni Ekiti State ni ọdun 1937..
wikipedia
yo
Ojú gba Adedeji ti nitori awọn iwe ti o kọ ni nipasẹ iwa ati iṣẹ ile wa ..
wikipedia
yo
A yàn gẹ́gẹ́ bí olùrànlọ́wọ́ a tún ìwé tó Academic Journal, Bookbird
wikipedia
yo
Ìwé ọdún 1986 "Moonlight Stories" sọ̀rọ̀ nípa just-so Stories ìdí tí ẹkùn fi pa lórí àti ìdí tí ìkarahun ìjàpá fi san.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
jẹ́ Olùkọ̀wé ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà.Àwọn ìtọ́kasíàwọn Olùkọ̀wé ará Nàìjíríàọdún Ọjọ́ìbí Kosi (àwọn ènìyàn Alààyè)..
wikipedia
yo
(Ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n, oṣù kejì, ọdún 1972 sí ọjọ́ kẹwàá, oṣù kẹta, ọdún 2019) jẹ́ ọmọ orílẹ̀èdè Nàìjíríà tí ó fi ìlú Canada ṣe ibùgbé..
wikipedia
yo
Ọ̀jọ̀gbọ́n, òńkọ̀wé, oníṣẹ́ lámèyítọ́ alátinúdá ni, òńkọ̀wé afẹ̀daṣẹ̀fẹ̀ àti òńkọ̀wé sínú ìwé ìròyìn àtìgbàdégbà..
wikipedia
yo
Òun ni òǹkọ̀wé ìwé Naija No January carry Last, àkójọpọ̀ àwọn àròkọ ìfẹ́daṣẹ̀fẹ̀ ọdún 2015..
wikipedia
yo
Adésànmí pàdánù ẹ̀mí rẹ̀ ní ọjọ́ Kẹwàá, oṣù kẹta, ọdún 2019 nínú ọkọ̀ bàlúù Ethiopian Airlines flights tí ó jábọ̀ ní kété tí ó gbéra.Ìtàn ìgbésí ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ Ọmọ bíbí ìlú iṣanlú ní ìjọba ìbílẹ̀ apá Ìlà Oòrùn Yagba ní ìpínlẹ̀ kogi, Nàìjíríà ni Adésànmí..
wikipedia
yo
O gba oye akoko ninu imo ipilẹ ẹda (BA.)ninu ede Faranse ni Yunifasiti ti Ilorin ni odun 1992, oye ijinle (MA)ninu ede Faranse ni Yunifasiti ti Ibadan ni odun 1998, ati oye ijinle giga ninu Eko Faranse ni Yunifasiti ti Bìrìtì, Columbia, Canada ni odun 2002ise Adésànmí di omo egbe ibudo imo ede Faranse fun ìṣèwádìí ni Afirika (French Institute for Research in Africa - Ifra) ni odun 1993 si odun 1997, and ibudo imo ede Faranse ni Ilu Apa guusu Afirika (South Africa) ni odun 1998 si 2000..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìmọ̀ lítíréṣọ̀ ìfarawéra ní Yunifásítì Ìjọba Ìpínlẹ̀ Pennsylvania, USA láàrín ọdún 2002 sí 2005..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2006, ó darapọ̀ mọ́ Yunifásítì Carleton gẹ́gẹ́ bi i ọ̀jọ̀gbọ́n Lítíréṣọ̀ àti ẹ̀kọ́ Ajeko Áfríkà..
wikipedia
yo
Oun ni oludari ibudo imọ Yunifasiti ti Eko ajẹmọ́ Afirika ki o to di Oloogbe..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún ni Adésànmí jẹ́ òńkọ̀wé tó ń kọ àwọn èrò rẹ̀ sínú ìwé ìròyìn Premium Times àti Sàhárà Reporters lóòrèkóòrè..
wikipedia
yo
Ofẹsẹ lo poju ninu awon aroko re, o se àtẹnumọ́ alakiyesi lori awon ohun koBọ́gbọ́nmu ti o sele ni agbo oṣelu ati iṣẹlẹ awujo orilẹede Naijiria.Awon ẹda to rin lati maa ko ero re le lori ni awon oloselu, awon egberun ati awon gbajumo awujo ti o se pataki..
wikipedia
yo
Ní osù Ọ̀wàrà, ọdún 2015, ó sọ̀rọ̀ lòdì sí ìgbésẹ̀ Emir tí Kano tẹ́lẹ̀ rí lámì Sanusi láti gbé ọmọdé ní ìyàwó di kókó ọ̀rọ̀, kódà Emir fún lésì lórí ọ̀rọ̀ náà..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2015, ó sọ̀rọ̀ lóri Ted Talk tí àkòrí ń jẹ́ "Ìlú Afirika ní i ìtẹ̀síwájú ti àgbáyé ní láti gbajúmọ̀.IKÚ àti ìyẹ́sí rẹ̀ Adésànmí kú ní ọjọ́ kẹwàá, Oṣù Ẹrẹ́nà, Ọdún 2019 nígbà tí bàlúù Ethiopian Airlines flights 302 jábọ̀ ní kété tí ó gbéra láti Addis Ababa sí Nairobi..
wikipedia
yo
Leyin iku re, awon onkowe kaakiri agbaye ko akojopo ewi ọ̀tàléẹ̀ri ti won pe ni (W|ọlá for a ológoṣẹ́) ni orile si iwe re akoko ti o te jade ni odun2001..
wikipedia
yo
Nyaaka Oono ati Uche Peter Umezurike ni won sise oloke akopọjo ewi naaakojopo awon iwe ti o ko nawọ́ and other Poems (oracle books, Lagos; 2001)You're Not A Country, Africa (Penguin Books; 2011)Naija No January carry Last (Parsíà Publishers; 2015)Who Owns The Problem? Africa and the struggle for Agency (Michigan State University Press; 2020).Àwọn àmì-èye tí ó gba ní 2001, ìwé Adésànmí's akoko The alàgbà and other Poems, gba ami eye ewì ẹgbẹ́ àwọn òǹkọ̀wé orilẹede Naijiria (Association of Nigerian authors' Poetry Prize)..
wikipedia
yo
Ni 2010, iwe re You're not a country, Africa (Penguin books, 2011), akojopo aroko, Sog orókè nibi ifilole Penguin fun African Writing in the Nonfiction Category.Ni 2017 Adésànmí ni o gba Canada Bureau of International Education Leadership Award..Àwọn Ìtọ́kasí awon Oludani ara Naijiria..
wikipedia
yo
Je Olukọwe ọmọ ile Naijiriaigbesi aye arakunrin naa Adesokan je Akowe to lori asa ile afizko nibi tótí je associate professor ti ṣiyèméjì Literature ni ile iwe giga ti Indiana Blooington.ẹ̀kọ́ní ọdun 1990, Akin losi ile iwe giga ti ilu Ibadan Adesokan gba ma ni odun 2003 ati Ph.D..
wikipedia
yo
Láti ilé ìwé gíga ti Cornell ní ọdún 2005 níbi tóti gba ẹ̀bùn gẹ́gẹ́bí àẹ̀kọ́ tó pegede jùlọ nínú Department rẹ̀ ni Theatre Arts..
wikipedia
yo
Arákùnrin náà gba èbù tí Faculty ti Arts àti àpapọ̀ Council ti Arts àti àṣà..Àmì ẹ̀yẹ Adesokan gba àmì ẹ̀yẹ ti PEN Freedom-To-Write ní ọdún 1998 àti àmì ẹ̀yẹ ti Lillian Hellman-Dashu Hammett Human Rights ní ọdún 1999.Ìtọ́kasí.àwọn olùkọ̀wé ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Chimaòwúrọ̀ Ngozi Adichie (;Ọjọ́ kẹẹ́dógún, Oṣù Ọ̀wàrà, ọdún 1977 ni wọ́n bí Chimaòwúrọ̀ Ngozi Adichie..
wikipedia
yo
Òǹkọ̀wé ni lára àwọn iṣẹ́ rẹ̀ ní ìwé ìtàn àròsọ, ìwé ìtàn àròsọ kúkúrú àti ìwé ìtàn àròsọ ajẹmọ́ ìṣẹ̀lẹ̀ gidi..
wikipedia
yo
Wọ́n ṣe àpèjúwe rẹ̀ nínú "Times in Literary Supment" gẹ́gẹ́ bíi ẹni tí ó tayọ jùlọ nínú àwọn ò̀kọ̀wé elé Gẹ̀ẹ́sì tí wọ́n jẹ́ òdò, tí ó sì ṣe àṣàṣ láti fojú àwọn owó ìran ìran tuntun mọ́ sí lítírétírérí Afrika, pàápàá jùlọ ní ibùdó rẹ̀ kejì kejì Nàìjíríeko àti iṣẹ́ rẹ̀ Adigbogbo tí kó àwọn ìwé ( Kòwe ní ọdún 2003, half of ọdún 2003 sun ní ọdún 2006 àti American 2006, ọdún 2013, ìbápọ̀ pé ìtàn the thing The PAM Adewe ní ọdún 2009 àti ọdún Adewe we should we should gi ní ọdún 2014.. ọdún 2014..
wikipedia
yo
Awon iwe re ti o je tuntun ni Dear Ijehelmina, or a Feminist Manifesto in Conwa suggestion ni odun 2017, Zìkóra ni odun 2020 ati Notes on Grief ni odun 2021..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2008, ó gba àmì ẹ̀yẹ ẹ̀tọ́ MacArthur genius Grant..
wikipedia
yo
Oun lo gba ami eye pen Pinter Prize ni ọdun 2018ilẹ̀ sekondiri Yunifasiti ti Naijiria, Nsukka ni Akinigbogbo ti pari ẹkọ sekondiri rẹ nibi ti o ti ọpọlọpọ ami ami ajẹmọ́ akadá..
wikipedia
yo
Ó kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìmọ̀ ìṣègùn òyìnbó àti ìmọ̀ nípa òògùn ní Yunifásitì ti Nàìjíríà fún ọdún kan àti abo. Ní àsìkò náà ni ó ṣiṣẹ́ Olóke ìwé ìròyìn Mididínlógójì tí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ Ìjọ Àgùdà ń ṣe àkoso rẹ̀..
wikipedia
yo
Ó kúrò ní orílẹ̀èdè Nàìjíríà lọ sí United States lọ́mọ ọdún mọ́kàndínlógún láti lọ kó ìmọ̀ ìbánisọ̀rọ̀ àti sáyẹ́ǹsì òṣèlú ní Yunifásítì Dreìdánwò ní Philadelphia Pennsylvania.Ní ọdún 2003, Adichie parí Èkó Oyè ìjìnlẹ̀ nínú àròkọ àtinúdá ní Yunifásítì John Hopkins.Ẹ̀bi rẹ̀ ọdún 2009 ni Adichie fẹ́ IVara Ẹ̀ṣẹ̀gé, Oníṣègùn Òyìnbó ọmọ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Adichie ń pín àsìkò rẹ̀ láàárín United States àti Nàìjíríà, níbi tí ó ń kọ́ àwọn èèyàn nípa àròkọ.Àwọn ìwé tí ó kọ tàbí kópa Brockes, Emma (4 March 2017)..
wikipedia
yo
Retrieved 22 August 2017."Chimaolùwádìí Ngozi Adichie"
wikipedia
yo
Retrieved 18 January 2014."Chimaolùwádìí Ngozi Adichie Biography ↑ List of Works, Study Guides & Essays ↑ Tíìgbésíverver..
wikipedia
yo
"ChimaLọ́dún Ngozi Adichie ↑ Biography, Books, & Facts"
wikipedia
yo
Archived from the original on 15 September 2012.COPnall, James (16 December 2011), "Steak knife", the times literary supplement, p..
wikipedia
yo
20.Àwọn ìtọ́kasíàwọn olukọwe ará Naijiri ọmọ Igbo..
wikipedia
yo
jẹ́ òǹkọ̀wé ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.Àwọn ìtọ́ka síàwọn Olùkọ̀wé ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Aliyu akílú M.f.R ti a bi ni odun 1918 ti o ṣaláìsí ni ojo Konkandilogun osu kewa odun 1999 ti a tun mo si Malam Akilu Aliyu tabi qq Aliyu ni o je akewi, ònkọ̀tàn, ojogbon ati oloselu omo orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
ó sì tún jẹ́ ọ̀kan pàtàkì láàrín àwọn akéwì ẹ̀yà Hausa lásìkò Twentieth Century.Nípa rẹ̀wọ́n bí Akliu Aliyu ní ìlú Jega ninu abúlé kan ti wón n pe ni (Kyarmi) àmọ́ tí ó ti di Ìpínlẹ̀ Kebbi lóde òní..
wikipedia
yo
Akilú lo púpọ̀ ìsẹ̀mí rẹ̀ ní ìlú Kano, níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìmọ̀ ẹ̀sìn Musulumi nígbà èwe rẹ̀..
wikipedia
yo
Ó wà ní ìlú Maiduguri fún àìmọye ọdún ṣáájú kí ó tó padà sí ìlú Kano níbi tí ó wà títí ó fi fàyè sílẹ̀..
wikipedia
yo
Òun ni ó dá ilé-ẹ̀kọ́ Azare sílẹ̀ ní ìlú Miadugbevjipọ̀.Àwọn òkọ̀wé ara Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Elechi Amadi (ọjọ́ kejìlá, oṣù Èbìbì, Olny 1934 – ​ ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n, oṣù òkúdù, ọdún 2016) jẹ́ òǹkọ̀wé àti jagunjagun ọmọ orílẹ̀èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Òǹkọ̀wé àwọn eré oníṣe àti ìtàn àròsọ ni tí wọ́n dálé ìgbéayé Abúlé Adúláwọ̀, iṣẹ́, ìgbàgbọ́ àti àwọn ìṣèsin ṣáájú ìbáṣepọ̀ ọ̀làjú Òyìnbó..
wikipedia
yo
Iṣẹ́ Amadi tí ó peregedé ní Ìwé Ìtàn Àròsọ tí í ṣe igi àkọ́ṣe rẹ̀ "The ètòbka” tí wọ́n sọ pé òún ló tayọ jù nínú ìtàn àròsọ.’
wikipedia
yo
O sise gege bi awon nigba kan ri, o si pada sise oluko ni opolopo ile eko, lara won ni ileile awon ologun ile Naijiria, ni ilu Zaria laarin odun 1963 - ​ 1966..
wikipedia
yo
Ó ṣiṣẹ́ olùkọ́ ní ilẹ̀ilẹ̀ Olùkọ́ni ti ìpínlẹ̀ Rivers Bákan tí ó ti jé alákòóso Agbo Ẹ̀ka ìmọ̀ Ajéré ọ̀nà, bákan náà olórí ẹ̀ka ẹ̀kọ́ Lítíréṣọ̀ àti Olùdarí ẹ̀kọ́ àṣekárí ológun àti òṣèlú Ámádì ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn ológun, ó sì dúró nibẹ̀ lásìkò ogun abẹ́lé Nàìjíríà, kí ó tó wá fẹ̀yìntì gẹ́gẹ́bí Ọ̀gágun..
wikipedia
yo
O lo si kọlẹji ijọba ni ọdun 1948 - 1952, bakan naa lọ lọ si Survey School ni Ilu Oyo, o tẹsiwaju si Yunifasiti ti Ibadan láàarín ọdun 1955 si ọdun ọdun 1959, o si gba oye Eko ninu ẹkọ físíìsì ati ẹkọ iṣiro.
wikipedia
yo
Àwọn ìwé tó kọ́ THE KABB (1966)The Great Ponds (1969)sun In Biafra (1973 (1973s of Johannesburg (1978)The slave (1978) (1986) and Agbo (2003'' (Àwọn ìtọ́pọ̀ ará Nàìjíríka ará kukuru..
wikipedia
yo
Sefi Atta (tí a bí ní Oṣù Kínní Ọdún 1964) jẹ́ olùkọ̀wé ará ìlú Nàìjíríà mọ́ Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Wọ́n ti túfọ̀ àwọn oríṣiríṣi èdè, wọ́n ti ka àwọn ìwé rẹ̀ lórí ẹ̀rọ asọ̀rọ̀ ma ìtànìgbésí bí BBC, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn eré ìtàgé tí ó ṣe ni wọ́n ti tún ṣe káàkiri àgbáyé..
wikipedia
yo
Awon ami eye ti o ti gba ni Wole Soyinka Prize for Literature in Africa ti odun 2006 ati Noma Award for Publishing in AFRICati odun 2009.Ìtàn igbesi aye re won bi Atta ni Ipinle Eko, orile-ede Naijiria, ni osu Kínní odun 1964, sinu idile omo marun-un..
wikipedia
yo
Baba rẹ, Abdul-Aziz Atta ni Akowe Ijọba Apapo Ile Naijiria titi di igba ti o fàyè silẹ ni ọdun 1972, iya rẹ, Iyabo Atta ni o to dagba.O lo ile-iwe Queen's College ti Ipinle Eko, ati Millfield School ni England..
wikipedia
yo
degree ní Birmingham University.O fẹ́ yeye Ransome-Kuti, Dokita ìsègùn òyìn, àti ọmọ Oroko Ransome-Kuti, wọ́n sì bí ọmọbìnrin kan, témi.Awon Ìtọ́kasí àwọn òkọ̀wé ará Nàìjíríàawọn ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
tí a bí ní ọjọ́ kejìlá Oṣù Keje ní Ìpínlẹ̀ Ábíá tí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà jẹ́ òkọ̀wé, adarí eré orí ìtàgé, ònkọ̀tàn àti ìká́ntẹ́
wikipedia
yo
O tún jẹ́ oníwàásù ní ìjọ Methodist ní ìlú Britain..
wikipedia
yo
Òun ni Olùdarí àti alágbàátẹ̀rù SAPm Publications Ltd..
wikipedia
yo
Oun naa ni oludasile ati ALÁBÒÓJÚTÓ Sentinel Poetry Movement ti o si tun jẹ oludasile ati Òǹtẹ̀wé Maasiini Nollywood Focus, Sentinel Literary Quarterly, Sentinel Nigeria ati Sentinel Champions.<Ref></Ref> itọkasi..
wikipedia
yo
Bàbáfẹ̀mí bádéjọ jẹ́ onímọ̀, ònkòwé àti aṣojú ọmọ orílẹ̀èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Wọ́n bí Ọ̀jọ̀gbọ́n Bàbáfẹ́mi Adésínà Kòléjọ ní ọjọ́ kẹrin, oṣù Ẹrẹ́nà, Ọdún 1955 ni Ìjẹ̀bú.ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ Ayé Bàbáfẹ́mi fígbèlé jẹ́ onímọ̀, ònkọ̀wé àti aṣojú ọmọ orílẹ̀èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Wọ́n bí Ọ̀jọ̀gbọ́n Bàbáfẹ́mi Adésínà Àljọ ní ọjọ́ kẹrin, oṣù Ẹrẹ́nà, ọdún 1955 ni Ìjẹ̀bú..
wikipedia
yo
Ó ṣe tán ní ilẹ̀ilẹ̀ girama Ìjẹ̀bú-Òde, ni Ìjẹ̀bú-Òde ki ó tẹ̀síwájú lati lọ si Yunifásítì ìjọba àpapọ̀ ẹ̀kọ́ lati gba oyè ẹ̀kọ́ nínú Sáyẹ́ńsì Òṣèlú..
wikipedia
yo
Bakan naa o pari oye Ph.D re ninu sayensi oselu ni Yunifasiti California, Los, (UCls), USA ni odun 1982, o gba oye Eko ninu eko imo ofin LL.B ni Yunifasiti Ijoba apapo ti ilu Eko, Naijiria ni osu ṣẹ́ẹ́rẹ́ odun 1990..
wikipedia
yo
O di ọmọ ẹgbẹ awon Amofin (Nigerian Bar) gege bi Amofin ati agbenuso ni ojo kejila, osu ope, odun 1990ebi ojogbon Babafemi bádéjo gbe AdeJùmọ̀kẹ́ Odusanya ni ojo Kesan-an, osu ọ̀wàrà, odun 1977, won ni omo mẹrin ati awon runran..
wikipedia
yo
Wọ́n jùmọ̀ dá yinTab Private Academy sílẹ̀, ilẹ̀ilẹ̀ fún àwọn ọmọ láti àkọ́bẹ̀rẹ̀ títí dé sẹ́kọ́ndírì.Iṣẹ́ ní ọjọ́ 2, oṣù ọ̀wàrà, ọdún 1991, Mínísítà fún àwọn ọ̀rọ̀ ajẹmọ́lùú tí orílẹ̀èdè Nàìjíríà búlu Ìkópa rẹ̀ nínú ìkẹrindínláàdọ́ta Àpérò ti ẹgbẹ́ un gbogbogbòò gẹ́gẹ́ bíi amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ ẹ̀ka iṣẹ́ sí ààrẹ orílẹ̀èdè tẹ̀lé Olusegun Obasanjo ni èròńgbà fún ipò akọ̀wé àjọ ìṣọ̀kan àgbáyé (un) ..
wikipedia
yo
O fi iṣẹ́ sílẹ̀ ní Yunifásítì Ìjọba Àpapọ̀ ti ìlú Èkó ní ọdún 1996, láti lọ gba iṣẹ́ ajẹmọ́ àlàáfíà ìlú ní Àjọ Ìṣọ̀kan Àgbáyé (ún), níbi tí ó ti fẹ̀yìntì ní ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n, oṣù Ẹrẹ́nà, ọdún 2017..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó wà ní ìlú Nairobi, Kẹ́nyà ni óósì ajẹmọ́ṣẹ́ Somaila, lára ọdún mọ́kànlá tí ó lò ó ṣiṣẹ́ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ agbègbè atakọ́ra lára wọn ní Somalia, Liberia, Guinea Bissau àti Darfur Sudan.Ìtọ́kasí 1. LISNArd (20 February 2014)..
wikipedia
yo
Biographical Legacy And Research Foundation Nigeria Móṣèf's Who's Who In Nigeria (Online)..
wikipedia
yo
Retrieved 12 September 2021Ephraim, Solutions (March 4, 2018)..
wikipedia
yo
Retrieved 12 September 2021.Crots, Winston (June 1987)..
wikipedia
yo
A History of the Department of Political Science University of California, Los Angeles 1920-1987..
wikipedia
yo
ISBN978-978-53163-0-81. ​ The humani 9780 (1 August In)..
wikipedia
yo
“UN envoy to facitalitate Dialogue within Divided v't..
wikipedia
yo
Retrieved 13 September 2021.1. The humanics (1 August 2005)..
wikipedia
yo
Retrieved 13 September 2021.22. Voice of America Archive (31 October 2009)..
wikipedia
yo
"Somali officials Discuss rẹ̀ló of government"
wikipedia
yo
Retrieved 12 September 2021.1. Voice of America Archive (31 October 2009)..
wikipedia
yo
Retrieved 12 September 2021.1. Babafemi, bádéjo (2019)..
wikipedia
yo
Retrieved 12 September 2021.1. Bled strategic Forum, 2019..
wikipedia
yo
"Chrisland University appoints bádéjo as first professor"
wikipedia
yo
Retrieved 12 September 2021.Senior adviser to the president of the court of the Prime minister of Bahrain, Kingdom of Bahrain and a board member of the Bahrain visions ForumLily, chen..
wikipedia
yo