cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Chinyere Ike Nwosu jẹ́ ọmọ Ológun ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó tifẹ̀yìntì àti Gómìnà àwọn Ìpínlẹ̀ Ábìà àti Oyo tẹ́lẹ̀.Ìtọ́kasí àwọn Gómìnà ìpínlẹ̀ Abiire Gómìnà ìpínlẹ̀..
wikipedia
yo
(1951-2021) je omo ile Naijiria ati gomina ipinle Oyo tele.Awon gomina ipinle Oyo..
wikipedia
yo
Làdi Onaolapo Adeṣina (20 January 1939 – 11 November 2012) jẹ oloselu ọmọ ilẹ̀ Naijiria ati gomina ipinlẹ Oyo tẹlẹ.Àwọn Gomina ìpínlẹ̀ Oyoàwọn oloselu ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Eyi ni àkójọ àwọn alakoso ati àwọn gomina ti Ipinle Eko..
wikipedia
yo
Lagos State was formed in 1967-05-27 from Colony Province and Lagos Federal territory.Wo eleyi naNigeriaStates of Nigerialist of all Nigerian state Governorṣàwọn itọkasiExternal Sọ́ọ̀lù Lagos State Government of Nigeria..
wikipedia
yo
Mojì Ohofun Johnson jẹ ọmọ ile Naijiria ati gomina ipinle Eko tẹlẹ.Awon Gomina ipinle Eko..
wikipedia
yo
Adekunle Shamutìtì Lawal jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàíjíríà àti gominà ìpínlẹ̀ Èkó tẹ́lẹ̀.ìtọ́ Gómìnà ìpínlẹ̀ ìmọ̀ Ògùn ìpínlẹ̀ Èkó Èkó..
wikipedia
yo
Nbuse Kanu (1943-2021) jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti Gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó tẹ́lẹ̀.Ìtọ́kasí Gómìnà ìpínlẹ̀ Imoàwọn Gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó..
wikipedia
yo
Okoh Ebitu Ukiwe (ọjọ́ 26 Oṣù kẹwá 1940) jẹ́ ọmọ ológun ilẹ̀ Nàìjíríà titifẹ̀yìntì àti igbákejì Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà àti gómìnà tẹ́lẹ̀ fún ìpín èkó àti ìpín Niger.Ìtọ́kasí igbákejì Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríààwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ nínrawọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó..
wikipedia
yo
Lateef Kayode Jakande (ojoibi 23 July 1929-2021) je omo ile Naijiria ati gomina ipinle Eko tele ati alakoso eto ise abele labe ijoba Sani Abacha.Awon itọkasiawon Gomina ipinle Eko..
wikipedia
yo
(eni ti a bi ni 18 October 1945 ti o si fàyèsile ni 23 September 2003) je omo ile Naijiria ati gomina ipinle Eko tele..
wikipedia
yo
O je gomina ipinle Eko laarin osu kinni odun 1984 si osu kejo odun 1986 nigba isejoba ologun Muhammadu Buhari ati Ibrahim Babangida.itọkasiawon gomina ipinle Eko..
wikipedia
yo
jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti igbákejì ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà àti gómìnà ìpínlẹ̀ èkó tẹ́lẹ̀.Ìtọ́kasí gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó..
wikipedia
yo
Ọ̀gágun Raji alágbe Ràsákì (ojoibi January 7, 1947) jẹ́ ọmọ ológun ti feyinti Ara orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó, Ondó àti Ogun tẹ́lẹ̀.Àwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkóàwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ lóde Gómìnà Ìpínlẹ̀ Òndó..
wikipedia
yo
Jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó tẹ́lẹ̀.Ìtọ́kasí sílu Ìpínlẹ̀ Èkó..
wikipedia
yo
Mohammed Buba Marwa (Ọjọ́ìbí September 9, 1953) jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti gómìnà àwọn Ìpínlẹ̀ Borno àti Èkó tẹ́lẹ̀.Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní1953àwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ Borno Ìpínlẹ̀ Ìpínlẹ̀ Ìpínlẹ̀ Èkó..
wikipedia
yo
Tabili ìsàlẹ̀ yí ṣàfihàn àkójọ àwọn orúkọ àlàje àwọn ìpínlẹ̀ Nàìjíríà.Ẹ tún wò..
wikipedia
yo
' Ní Yunifásítì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ìtọ́kasí Yunifásítì ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Abti - American University of Nigeria ni Yunifásítì YDanidani ni orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ìtọ́kasí Yunifásítì ni Nàìjíríà..
wikipedia
yo
‘ jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìjọ̀dún ìjọba ní orílẹ̀-èdè Nàígbé̀npọ̀ ní Nàíjíríà-èdè
wikipedia
yo
Ní Yunifásítì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Àwọn ìtọ́ka síAmbrose Alli..
wikipedia
yo
Ní Yunifásítì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ìtọ́kasíYunifásítì ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Yunifasiti ti Ipinle Cross River ti a tun mọ si uniCross jẹ ile-eko giga ti ijoba ti o ni awon ile-eko giga merin ti o tan kaakiri awon ijoba ibile merin ti Ipinle naa..
wikipedia
yo
Ilé-ẹ̀kọ́ gíga tí a mọ̀ tẹ́lẹ̀ sí Cross River University of Technology (Crutech)..
wikipedia
yo
O tun orukọ rẹ ni ni Oṣu Keji ọdun 2021 nipasẹ àbádòfin ti o kọja ni Ile-igbimọ aṣofin Ipinle Cross River eyiti Gomina Ipinle naa, Benedict Ayade fọwọsi lẹhin naa..
wikipedia
yo
Ìyípadà ti orúkọ Ilé-ẹ̀kọ́ gíga ni lati jẹ́ ki iṣẹ́ Fásitì ṣiṣẹ́ bi ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti àṣà, èyítí ó pèsè àyè láti fúnni ní àwọn iṣẹ́ ìkẹ́kọ̀ọ́ díẹ̀ síi dípò ìdojúkọ lórí àwọn iṣẹ́ ìkẹ́kọ̀ọ́ ti ìmọ̀-ẹ̀rọ.Ilé-ẹ̀kọ́ gíga gba orúkọ abínibí ti ìpínlẹ̀ náà padà ti ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti ìpínlẹ̀ Cross River, Uyo ni báyìí Yunifásítì ti Uyo, Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom, Nàìjíríà títí di ọjọ́ kìíní oṣù Kẹwàá ọdún 1991 nígbà tí ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà dá Fásitì ti Uyo sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ilé-ẹ̀kọ́ gíga àpapọ̀ lẹ́hìn ìpinyà ti ila Akwa Ibom láti ìpínlẹ̀ Cross River ní ọdún 1987..
wikipedia
yo
Ile-ẹkọ giga ti Uyo jogún awọn ọmọ ile-iwe, oṣiṣẹ, awọn eto ẹkọ ati gbogbo awọn ohun elo ti Ile-ẹkọ giga ti Ipinle Cross River nigba naa ti iṣeto nipasẹ Ipinle Cross River ni ọdun 1983.itọkasiYunifasiti ni Naijiria..
wikipedia
yo
jẹ́ ọ̀kan lára àwọn Yunifásítì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ìtọ́kasíYunifásítì ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ní Yunifásítì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ní oṣù April, ọdún 2023, ọ̀gbẹ́ni Charles adeléye tó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́rin dín lọ́gọ́ta ni a fi jẹ́ rẹ́gístrar tuntun fún ilé ìwé gíga náà tí ọ̀gbẹ́ni Robert Awoyẹmí tó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́ta Leekú jẹ́ Alákoso yàrá ìkàwé tuntun ta ṣẹ̀ṣẹ̀ yàn.Mogatọ́kasí ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ti a tun mọ si LASU, wa ni ọjọ, ilu kan ni Ipinle Eko, Nigeria..
wikipedia
yo
Ile-ẹkọ giga ti dasilẹ ni ọdun 1983 nipasẹ Ofin ti o fun laaye ni Ipinle Eko, fun ilọsiwaju ti Eko ati idasilẹ didara ẹkọ giga; gbolohun ọrọ rẹ jẹ fun otitọ ati iṣe.itọkasiYunifasiti ni Naijiria..
wikipedia
yo
Yunifasiti Olabisi Onabanjo je ile iwe giga ti ipinle Ogun ni orile ede Naijiria.Awon itọkasiYunifásítì ni Naijirika kukuru..
wikipedia
yo
A dá kalẹ̀ ní ọdún 1988 bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn akẹ́kọ àkọ́kọ́ ṣe ayẹyẹ ìwọlé ní ọdún 1990 tí iṣẹ́ sì bẹ̀rẹ̀ ní ọdún na..
wikipedia
yo
Orúkọ Olórí Yunifásítì ti ìlú Abuja Lọ́wọ́lọ́wọ́ ni Ọ̀jọ̀gbọ́n AbdulRashheed na'Allah , ìjọba rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kini, oṣù keje, ọdún 2019(July 1, 2019)..
wikipedia
yo
Yunifásítì Abuja ní ọgbà méjì(Main Campus àti Mini Campus)..
wikipedia
yo
Mini Campus wa ni ìlú Gvaowalàdá, main Campus sì wà ní ọ́nà Abuja-Airpot..
wikipedia
yo
Yunifásítì ìlú Àbújá ní ilé tí ó kọjá ẹgbẹ̀rún mọ́kànlá hectare Ilẹ̀(Over 11, 000 hectares) èyí tí ó mú wọn jẹ́ Yunifásítì Kejì tí ó ní ilé jù ní Nàìjíríà .Ilé ìkàwé á dá ilé ìkàwé yunfisiti náà kalẹ̀ ní ọdún 1988 láti gbárùkù ti kíkọ́,omi ari ìwádí èyíbẹ̀rẹ̀ ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ète yunyunfisiti ìlú Àbújá nípa pípèsè àwọn ohun tí kòkọ́ko nílò fún ẹ̀kọ́ ni lort ẹ̀rọ jùjù àti ìwé tí ènìyàn lè dìmú.Àwọn ìtọ́kasíjìnnà..
wikipedia
yo
jẹ́ yunifásítì ìjọba ní ìlú Benin, ìpínlẹ̀ Ẹdó ní orílẹ̀-èdè Nàíjírìa..
wikipedia
yo
Ada kalẹ̀ ní ọjọ́ kíní, oṣù keje, ọdún 1970photo Galleryitọ́kasíbẹ̀ninBenin..
wikipedia
yo
jẹ Yunifasiti ijoba ti o wa ni Calabar, Ipinle Cross River, orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
Oruko olori Yunifasiti naa lowolowo ni ojogbon Florence Obi , ojogbon Florence di olori Yunifasiti naa ni ojo kini, osu kejila, odun 2020 (Dec 1, 2020).itọkasiYunifasiti ni Naijiria..
wikipedia
yo
jẹ́ yunifásítì ti ìjọba tí ó wà ní ìpínlẹ̀ Kwara, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Orúkọ olórí yunifásitì ÌLỌRIN Lọ́wọ́lọ́wọ́ ní Ọ̀JỌ̀GBỌ́N Wahab Ola' Egbẹ́..
wikipedia
yo
Yunifásítì Ìlọrin ní ọlẹ̀ ní àádọ́ta ẹgbẹ̀rún akẹ́kọ Ó sì tún ní ọlẹ̀ ní ẹgbẹ̀rún mẹ́ẹ̀dógún hectare ilé(15, 000 hectares), èyí tí ó mú wọn jẹ́ Yunifásítì tí ó ní ilé jù ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ..Àwọn Ìtọ́kasí Yunifásítì ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O bere bi ogba Yunifasiti iluIbadanni osu Kọkànlá, odun1971, odun 1971 ..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1975, ìjọba ológun ìgbanáà dá kalẹ̀ gẹ́gẹ́bí Yunifásítì, Ọ̀jọ̀gbọ́n Gilbert Odunaguchi ṣì jẹ́ olórí àkọ́kọ́ Yunifásítì náà ..
wikipedia
yo
Orúkọ Olóri Yunifásítì náà lọ́wọ́lọ́wọ́ ni Ọ̀jọ̀gbọ́n tànko IsháyàtótóYunifásítì ni Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Yunifasiti ilu Maiduguri je Yunifasiti ni orile-ede Naijiria, ti o wa ni ilu Maiduguri ni ipinle Borno..
wikipedia
yo
A da kalè(pẹlu awọn Yunifasiti mefa miran) ni ọdun 1975 , olori Yunifasiti naa ni ojogbon Aliyu Shugaàwọn itọkasiYunifasiti ni Naijiria..
wikipedia
yo
Yunifasiti ilu Port Harcourt je Yunifasiti ijoba ti okale si ilu Port Harcourt, Ipinle Delta ni orile-ede Naijiria.Ìtọ́kasíYunifasiti ni Naijiria..
wikipedia
yo
jẹ́ yunifásítì tí ó kalẹ̀ sí Adó-Èkìtì, Ìpínlẹ̀ Èkìtì, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Orúkọ olórí Yunifásítì náà lọ́wọ́lọ́wọ́ ni Ọ̀jọ̀gbọ́n Edward Ọlánípeku Yunifásítì ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Yunifásítì Covenant jẹ́ Yunifásítì aládàáni kan tí ó wà ní Ìpínlẹ̀ Ògùn ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Àwọn ìtọ́kasíYunifásítì ní Nàìjíríàdi kúkúrú..
wikipedia
yo
Àkójọpọ̀ àwọn ìlú ní Nàìjíríàèyí ni àkójọpọ̀ àwọn ìlú àti Olú-Ìlú ní Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Awon ilu mẹrinla ti o ni opo olugbe ni a se afihan won daadaa.itọkasi..
wikipedia
yo
jẹ́ ìlú ní Nàìjíríà.Ìtọ́kasíàwọn ìlú àti abúlé ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
je ilu ni Naijiria ni apa gugúṣù iwoorun ti ijoba ipinle Akwa ibomáwọn eniyan awon eniyan ti gbe Abasi je akojopo eya Ibibio pelu oniruuru asa adayeba ati atọwọdọwọ..
wikipedia
yo
Biotilejepe gbe Abaṣi, tele jẹ ipa ti ilu olokiki opobo Kingdom, wa tele lori iwe itọkasi aye ṣaaju akoko 1929, ti awọn obirin lodi si olori amunisin ti Naijiria ni ọdun 1929 jẹ lati pese siwaju titari sinu ọla fun ilu yi.
wikipedia
yo
mẹ́ta-mẹ́rin ti ọ̀rúndún sẹ́yìn, kẹrìnjì akórìsì jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ìlú wọnnì ní àwọn ìgbèríko tí yíò ati Owerri, tí àwọn obìrin fi ìgboyà tàpá sí ohun tí àwọn olórí amúnisìn nṣe kí Nàìjíríà ọ̀tọ̀ di òmìnira..
wikipedia
yo
Ìgbìyànjú àwọn obìrin láti Susu àwọn ìletò enia yọrí sí ikú..
wikipedia
yo
Awon obirin merin le logun ni won yinbon pa.ohun Igbaoba ajeitọkasiawon ilu ati Abule ni Naijiria..
wikipedia
yo
jẹ ilu ni Naijiria.itọkasiàwọn ilu ati abule ni Naijiria..
wikipedia
yo
jẹ ilu ni Naijiria.itọkasi awọn ilu ati abule ni Naijiria..
wikipedia
yo
jẹ ilu ni Naijiria.Itọ̀ ilu ati Abule ni Naijiria..
wikipedia
yo
Ikorodu jẹ ìlú ní Nàìjíríà.Àwòrán ìtọ́kasíàwọn ìlú àti abúlé ní Ìpínlẹ̀ Èkó..
wikipedia
yo
Ikoyi jẹ ilu ni Naijiria.Itọ̀ ilu ati Abule ni Ipinle Eko..
wikipedia
yo
jẹ ilu ni IpinleOgun, Naijiria.Awon ilu ilu ati Naijiria ni Naijiria..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀bo jẹ́ ìlú ni Nàìjíríà.galleryítọ́kasíàwọn ìlú àti abúlé ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
jẹ́ ìlú olórúkọ ní ìpínlẹ̀ Ògùn Nàìjíríà.Ìtọ́kasíàwọn ìlú àti abúlé ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
jẹ ìlú to tóbi jù ni Ìjọba ibilẹ Gúsù nítorí ti Òkè-Ogun ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ , Nàìjíríà...
wikipedia
yo
Àwọn ọmọ Yorùbá ti ṣeẹlẹ̀lẹjọ tan mọ́ àwọn Jèhófà ti Dahomey àti àwọn ifọ̀n ni Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ..
wikipedia
yo
Oloye won oba ilu naa wa lati idile Ọbàtálá, Ọbalúfọ̀n ti Ọ̀yọ́ ilẹ̀..
wikipedia
yo
Ṣepẹtẹrí dúró láàrin ìgbq, àgọ́-Àmọ́dù àti oje Owode (tí wọ́n pè ní “aha” tẹ́lẹ̀) tẹ́lẹ̀ ṣákì, àgọ́-are àti ìsẹ̀yín.Àpèjúwe orúkọ tí ọba ṣepẹtẹrí njẹ́ ní Ọbalùfọ̀n ti ṣepẹtẹrí..
wikipedia
yo
Àwọn ìdílé tó ńṣe jọba ní dáódus, Balóguns àti Orosrosọ wa ni aarin ṣákì àti Igboho ni agbègbè Òkè-ogun, Ọ̀yọ́ arẹwà Senatorial District ti ìlú Oyo ni Yorùbá..
wikipedia
yo
Agbegbe ṣepẹtẹrí BÉÈRÈ lati ìsẹ̀yín Oòsì Lopin ni bakasẹ, ilu kekere kan pẹlu aala ti Ipinle Oyo ati Ipinle Kwara.Awon ara ilu ilu je Ìbaràpópó ti o ni akoko, awon eniyan ti o je ti ẹya Yoruba ti won so ede Yoruba, botilẹjẹpe awon egbe to kere lati ibòun ni Nigeria ati Afirika ni asoju..
wikipedia
yo
Bíi gbogbo àwọn ọmọ Yorùbá mìíràn, wọ́n jẹ́ ọmọ láti Odùduwà..
wikipedia
yo
Eto idile ti o gbooro se pataki si asa ati igbagbọ ile Yoruba.Iṣowo[Edit Source] wiwa ti nkan alumọni wa ni agbegbe, bii Saïté, columbite, Faoritete, KaPẹ̀tẹ́lẹ̀, ati Granite..
wikipedia
yo
Ijoba Ipinle Oyo ti n ṣeto Lapidary kan lati toju awọn nǹkan alumọni ati ọja òkúta iyebiye ni kariaye ni iluIbadan Ibadan nibiti awọn ìwakùsà le ṣe ta ọja wọn.Iṣẹ agbe ni iṣe awọn ọmọ ilu ṣeẹlẹ̀..
wikipedia
yo
Yato si awọn ipa akọkọ ti pípèsè ounjẹ ati ibi aabo, òòjọ́, awọn ohun elo aise ile-iṣẹ, o tun jẹ orisun pataki ti owo-wiwọle ni ijoba agbegbe.itọkasiàwọn ilu ati abule ni Naijiria..
wikipedia
yo
SÚLÈJA jẹ́ ìlú ní ìpínlẹ Niger, Nàìjíríà.ìtọ́kasí àwọn ìlú àti abúlé ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
jẹ́ ìlú ní Nàìjíríà.Aworanítokasiàwọn ìlú àti abúlé ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
}}Frederick John Dealtry Lugard, 1st Baron Lugard (22 January January 1858 – 11 April 1945), ti wọ́n mọ̀ sí sir Frederick Lugard Láàárín 1901 àti 1928, jẹ́ jagunjagun British , alágbàṣe , oluwakiri Afirika àti alámòójútó ìjọba amúnisi..
wikipedia
yo
O jẹ Gomina Hong Kong tẹ́lẹ̀ ri (1907-1912), Gomina ìkẹyìn Southern Nigeria Prounctorate (1912-1914), Komisona giga akọkọ (1900-1906) ati Gomina Ìkẹyìn (1912-1914) Northern Nigeria Provctorate]] ati adari Gomina Naijiria (1914–1919) Akokojoìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ Aye ati Ekowon bi Lugard ni Madras (Chennai nísìnyí) ni India, ṣugbọn won to o ni Worcester, England..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọmọkùnrin Reverend Frederick Grug Lugard, àlùfáà àwọn ológun biritéènì ní Madras, àti ìyàwó rẹ̀ kẹta Mary Howard (1819-1865), ọmọbìnrin Reverend John Garton Howard tí ó kéré jùlọ (1786-1862), ọmọkùnrin kékeré Omooba láti Thorne àti Melbourne nítòsí York..
wikipedia
yo
Arákùnrin bàbá rẹ̀ ní Sir Edward Lugard, Adjutant-General in India láti 1857 sí 1858 àti Permanent Under-secretary of State for War ní ilé-iṣẹ́ ogun láti 1861 di 1871..
wikipedia
yo
Lugard kẹ́kọ̀ọ́ ni Bssall School àti Royal Military College, Sandhurst..
wikipedia
yo
Orúkọ 'Dealtry' jẹ́ ìmọrírì Thomas Dealtry, ọ̀rẹ́ bàbá rẹ̀.Ìtọ́kasí ará Britani..
wikipedia
yo
je gomina ipinle Gombe lati October 7, 1996 titi de August 1998.Awon Gomina ipinle Gombe..
wikipedia
yo
Mohammed Báwa (6 April 1954 - 26 May 2017) jẹ́ gomina ìpínlẹ̀ Gombe lati August 1998 títí de May 1999.Ìtọ́kasí ́ji awon gomina ipinle Ekiti ipinleAwon ipinle (awon gomina..
wikipedia
yo
Je gomina ipinle Gombe lati May 29, 1999titi de May May 29, 2003.Awon Gomina ipinle Gombe..
wikipedia
yo
Ilu yi ni ìbúJoke agbegbe ijoba ibile Afiji.itọkasiàwọn ilu ati abule ni Ipinle Oyo..
wikipedia
yo
Ile-igbimọ aṣofin Ipinle Oyo ni apa ijọba ipinlẹ Oyo to n ṣe ofin ni ipinlẹ na gẹgẹ bi ilana-ìgbàgbépo Naijiria 1999 ṣe sọ..
wikipedia
yo
Alapefèé Olade Araọdún jẹ́ olóṣèlú ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti igbákejì sí gómìnà ìpínlẹ̀ Oyo, Adebayo Àlàó-àkàlà láti 2007..
wikipedia
yo
Tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀, o je asoju ni ile-igbimọ aṣofin Naijiria fun Ibadan South-West/Ibadan North-West Constituiyì lati 2003 de 2007 ati Alaga, agbegbe ijoba ibile guusu-iwoorun Ibadan ni 1999 de 2003.itọkacasal ni 2005 awon oloselu ara Naijiria..
wikipedia
yo
Agbegbe ijoba ibile guusu idẹmili je ijoba ibile ni ipinle Anambra ni Naijiria..
wikipedia
yo
Agbegbe ijoba ibile Ido-osi je ijoba ibile ni ipinle Ekiti to wa ni Naijiria..
wikipedia
yo
ibùjókò ó ré wà ní ìlú u Ido-òṣì/Iru-òsì wà ní Ìpínlẹ̀ Èkìtì, l'órílẹ̀ èdè Nàìjíríà.Ìjọba ìbílẹ̀ na a kún fún àwọn ìlú àti ìletò Atètèdì tí ó kúndùn-ún ẹ̀kọ́ kíkọ́, tí wọ́n sì ní ìdáwá a àkójọpọ̀ ó àwọn ọ̀mọ̀wé gíga yíká orílẹ̀ èdè ná a, tó sì tún jẹ́ ọ̀kan nínú u agbègbè ìjọba Ìpínlẹ̀ Èkìtì..
wikipedia
yo
Ó sún mọ́ àwọn agbègbè ìjọba mìíràn bí i mobá, Ìjerò, iléjẹ́meje ati àdó..
wikipedia
yo
Olú ilé iṣẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ yí i ni wọ́n fi s'odò sí Ido Èkìtì, tí ilẹ̀ ìṣàkóso sì wà ní Àárín-in ìlú Idò àti Usi..
wikipedia
yo
Láàrin-in àwọn akẹgbẹ́ ẹ̀ rẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Èkìtì, Ìdò-Òṣì ni àwọn onímọ̀ ìwé dunjú l'Àtàrí I Àtètèdà á ilé ìjọsìn àti ilé ẹ̀kọ́ alákọ́ọ̀bẹ̀rẹ̀ s'ìlú U Usi Ekiti ní kété tí ilé ẹ̀kọ́ ò ti Adó Èkìtì, ti ń se Olú-Ìlú Ìpínlẹ̀ ná A, gbìn'lé..
wikipedia
yo