cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ní Yunifásítì Ìbàdàn, ó ṣojú gbọ̀gán ibùgbé rẹ̀ ní ẹgbẹ́ aṣojú àwọn akẹ́kọ̀ọ́, ó sì jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ olótùú ti Alágasíni ti àwọn akẹ́kọ̀ọ́ nínú ọgbà ilé ẹ̀kọ́.Ipa rẹ̀ nínú ìṣèlúnígbà tí ó parí ẹ̀kọ dìgírì nínú ètò ọ̀rọ̀ ajé fàláé darapọ̀ mọ́ àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba gẹ́gẹ́ bí igbákejì akọ̀wé, ẹgbẹ́ àwọn àpapọ̀ àwọn òṣìṣẹ́ orílẹ̀èdè..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1971, wọ́n gbé lọ sí iléeṣẹ́ ìṣètò gbòógì (Central Planning Office)..
wikipedia
yo
Lásìkò rẹ̀ ni iléeṣẹ́ yìí, ẹ̀ka yìí kópa nínú ìgbékalẹ̀ ètò ìdàgbàsókè fún orílẹ̀èdè ìkẹta (Third National Development Plan) àti ṣíṣe àtúnyẹ̀wò iṣẹ́ tí ìjọba bá ti yí padà..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1977, wọ́n yàn Fáláé gẹ́gẹ́bí akọ̀wé àgbà (Ẹ̀ka Oro - Aje), Oófi àwọn aṣojú ìjọba..
wikipedia
yo
Ni ọdun, o di oludari agba banki Nigerian Merchant, ti a mọ si United Dominion Trust..
wikipedia
yo
Lásìkò ìṣàkóso rẹ̀ ní báńkì náà, iléeṣẹ́ náà mú àlékún bá owó yíyà tí wọ́n fi àṣẹ sí..
wikipedia
yo
Fáláé padà sí iṣẹ́ ìjọba ní ọdún 1986, nígbà tí wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bíi akọ̀wé fún ìjọba..
wikipedia
yo
Lásìkò yìí, ó lérò wí pé Nàìjíríà nílò àtúntò ọ̀rọ̀ - ajé..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1985, ṣáájú ìgbàa rẹ̀, ìjọba ológun béèrè fún èrò àwùjọ ti imf (èròǹgbà àtúnṣe ọrọ-ajé) Economic structuring Pháàṣàsal gẹ́gẹ́ bíi ìdí fún owó yíyà láti ara owó náà..
wikipedia
yo
Ìjọba tó ń ṣàkóso nígbà yẹn gbé ètò àtúnṣe àgbékalẹ̀- structural adjustment Programme (Sap)..
wikipedia
yo
O fi ipo akọwe ijọba silẹ lati ṣe Minisita eto Ọ̀wọ́nna Ijọba apapọ ni ọdun 1990 ni asiko ijọba ologun Ibrahim Babaginda..
wikipedia
yo
Léhìn náà, ó darapọ̀ mọ́ ètò ìyípadà ìjọba àwarawa.àwọn ìtọ́ka síàwọn ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ngozi ọkọn-iweala ti won bi ni ojo ketala osu kefa odun 1954 je onimo eto isuna, o si tun je alákòóso fun eto inawo ati alákòóso fun oro ile okere tele fun orile-ede nria ..
wikipedia
yo
O jẹ ikan láàarín awọn adari ni standard Chartered bank, Twitter, global Alliance for vaccines and immunizations ati African risk capacity (Arc).Okorin - iweAla ti si se gege bi ojise nipa oro owo ni e meji ni abe akoso awon Aare ile Naijiria tele, Olusegun Obasanjo ati Goodluck Jonathan.ibẹrẹ Ayeibẹrẹ ati eto-ẹkọ rẹ won bii si Ogwashi-Ukwu ni Ipinle Delta ni Naijiria..
wikipedia
yo
Baba rẹ̀ ni Professor Chukwuka ọkọn ti ó jẹ́ Ọba láti ìdílé Ọbahai ní Ogwashi-Ukwu..
wikipedia
yo
Anne's School ní Ìbàdàn àti International School ní Ìbàdàn..
wikipedia
yo
O lọ si ile eko giga ti Harvard University ni USA ni ọdun 1978, o si gboye ninu Economics ni ọdun 1976..
wikipedia
yo
Ni ọdun 1981, o gba PhD ninu Regional Economics and Development lati Massa Institute of Technology (MIT)..
wikipedia
yo
Ó gba ìrànlọ́wọ́ láti ọ̀dọ American Association of University Women tí ó fi tẹ̀ síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀..
wikipedia
yo
Ike ba iweala, wọ́n sì bíi ọmọ mẹrin.Iṣẹ́ Ọkọ̀rin Ìwéala tí sì ṣe fún ilé ìfowópamọ́ ti àgbáyé fún ọdún mẹẹdọgbọn, ó sì gba ipò keji gẹ́gẹ́ bí Adari..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2010, ó di alága fún ìdá Replẹnidò, èyí tí wọ́n fi fún $49.3 billion fún àwọn orílẹ̀ èdè tó tálákà jùlọ..
wikipedia
yo
Ní ìgbà tí ó wà ní ilé ìfowópamọ́ àgbáyé, ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Effect development Cooperation with Africa..
wikipedia
yo
ỌkọNN ṣe minisita fun ọrọ̀ owó ní Nàìjíríà ní e méjì, ó sì tún ṣe mínísítà fún ètò orò ilẹ̀ òkèèrè..
wikipedia
yo
Oun lo siwaju ijiroro pẹlu Paris Club, eyi ti o fi jẹ ki wọn fagile soṣẹ $30billion ti Naijiria je..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2003, o gbiyanju lati jẹ ki idagbasoke wa ninu owo ti Naijiria gba nipa tita epo rọ̀bi, o ṣe òfin pe ti wọn ba ta iye owo kan, pe ki wọn fi si ile ifọwapamọ..
wikipedia
yo
Ó tún ṣe ìfihàn àwọn owó ti Ìpínlẹ̀ kan kan gbà sínú ìwé ìròyìn..
wikipedia
yo
pẹ̀lú àtìlẹ́yìn láti owó ilé ìfowópamọ́ àgbáyé àti íf ti ìjọba Nàìjíríà, ó dẹ́kun jìbìtì tí àwọn kan ṣe nípa gbígba owó fún àwọn òṣìṣẹ́ tí kò sí..
wikipedia
yo
Ó di adarí fún ilé ìfowópamọ́ àgbáyé ní Oṣù kejìlá ọdún 2007..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2011, wọn tun fi jẹ Minista fun ọrọ owo ni igba keji..
wikipedia
yo
Ó pèsè iṣẹ́ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn nípa ètò Youth Enterprise With Innovation (Youwin), ó sì rán àwọn obìnrin àti ọ̀dọ́ nípa ètò growing girls and women in Nigeria (Gwin)..
wikipedia
yo
O ri ọpọlọpọ wahala nigba ti won fi owo le epo ni 2012..
wikipedia
yo
Okon je ikan lara awon Alaga fun Global Commission for the economy and Clímate ati partnership for Effect development Cooperation..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2015 - 2016, ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ international Commission on Financing global education opportunities..
wikipedia
yo
Okon - iweala ni oludasile noi-Polls ati Centre for the Study of Economics of Africa (C-Sea)..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2012, ó du ipò olùdarí fún ilé iṣẹ́ ìfowópamọ́ ti àgbáyé..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2019, ó dára pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ UNESCO’s international Commission on the Future of education..
wikipedia
yo
Ni odun 2020, oludari Imf, Kristalina Georgieva fi ọkọNjo se ikan lara awon onimoran fun awon idojukọ ninu eto imulo wọn..
wikipedia
yo
Ellen Johnson-sirleaf (ojoibi 29 September, 1938) ni Aare ilẹ Liberia lọwọlọwọ.Ìtọ́kasí awọn Aare ilẹ laiberemejeàwọn ẹlẹ́bùn Nobel fun alafia..
wikipedia
yo
Konstanhún AlexAnd Kkaramanlis (Ọjọ́ìbí September 14, 1956) jẹ́ olóṣèlú Ọmọ Ilẹ̀ Griisi àti Alakoso Àgbà Ilẹ̀ Griisi lati 10 March 2004 títí dé 5 October, 2009.Ìtọ́kasí àwọn Gkọ́lọ́fín..
wikipedia
yo
Mamal Abdel Nasser (; ; – January 15, 1918 September 28, 1970) ni Aare orilẹ-ede Egypti lati ọdun 1956 de 1970.Àwọn itọkasi àwọn ara Egypt..
wikipedia
yo
2009 New Year's Card by David Revoy.jpg2009 (EEW]Meji tàbí ẹ̀sanlélẹ́gbẹ̀rúnmeji tabi egberun meji le léesan) je odun towopo to bere ni Ọjọ́bọ̀ ninu KÀLẸ́ŃDÀ Gregory.2009..
wikipedia
yo
Ẹ̀bùn man Booker fún ìtàn àròsọ tàbí ẹ̀bùn Booker ní ṣókí jẹ́ ẹ̀bùn ìwé kíkọ.
wikipedia
yo
Okan (1) je nọmba, iye tabi ònkà ati ami ribiribiph to duro fun ònkà naa.01..
wikipedia
yo
eji (2) jẹ́ nọmba, iye ati ohunomiph to duro fun nọmba naa..
wikipedia
yo
O je nọmba adabayé to tẹ̀lé okan (1) ṣugbọn to siwaju ẹ̀tá (3).02..
wikipedia
yo
Nicolas Sarkozy, Abase Omoba Ile Andorra (ríràtọrọ , Orúkọ àbísọ Nicolas Paul Stéphane Sarkozy de Nagybo-CSA ni 28 Oṣù Kínní, 1955) ni Ààrẹ ilé Fránsì láti 2007 dé 2012 àti nítoríre Abase Ọmọba Ilẹ̀ Andorra láti 2007 dé 2012..
wikipedia
yo
O gun ori aga ni 16 osu karun, 2007 leyin to bori candidate segolene ti egbe so nisia ni ojo 10 sẹ́yìn.Igbe Ayeitan ebi re Sarkozy je ara Fránsì aládàlú eyan eniyan..
wikipedia
yo
Ọmọ pál Iist er sárko sárzy De Nagyboc, tó olóyè ara hùngari, àti Andrée Jeanne “Da” Mallah (ọjọ́ 12 Oṣù Kẹ̀wá, 1925 ní Paris), tó jẹ́ ara Fránsì ẹlẹ́sìn kátólik àti ju Logdík láti Ottoman..
wikipedia
yo
Wọ́n fẹ́ rà wọ́n ní Saint-François-de-sales, Paris kọjá, ní 8 Oṣù Kejì, 1950 wọ́n ṣu kọ́ra wọn sílẹ̀ ní 1959.Ìtọ́kasí àwọn Ààrẹ ilẹ̀ Fránsì..
wikipedia
yo
Ẹta (3) jẹ́ nọ́mbà, iyè àti ríútọ̀ to dúrò fún nọ́mbà náà..
wikipedia
yo
O je nọmba adabayé to tẹle eji (2) ṣugbọn to ṣiwaju Erin (4).03..
wikipedia
yo
Colin Luther Powell ti wọ́n bí (ọjọ́ 5 April, 1937 – Oṣù kẹwá ọjọ́ 18, Ọdún 2021) jẹ́ ẹni àyẹ́sí ọmọ ilẹ̀ Amẹ́ríkà àti Ọ̀gágun oníràwọ̀ mẹ́rin tó ti fẹ̀yìntì kúrò ní ilé-iṣẹ́ ológun jagunjagun ilẹ̀ Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
O tun jẹ alakoso ọrọ okere ile Amerika lati 2001 – 2005 labẹ Aare George W..
wikipedia
yo
Nigbati wà ni ẹnu iṣẹ́ ológun, Powell tún jẹ́ alábàágbìmọ̀pọ̀ ọ̀rọ̀ abo orílẹ̀-èdè ilẹ̀ Amẹ́ríkà (National Security Advisor, 1987–1989); Ause, ilé-iṣẹ́ aláṣẹ àwọn ológun jagunjagun ilẹ̀ Amẹ́ríkà (U.S..
wikipedia
yo
Army forces Command, 1989); ati Alaga Ijokopapo awon oga ọmọ-ologun ilẹ̀ Amẹrika (chairman, U.S..
wikipedia
yo
Joint Chiefs of Staff, 1989–1993), Ori ipo yi lowa nigbati ogun ikun Odò Persia ṣẹlẹ..
wikipedia
yo
Ohun ni ó jẹ́ ẹni Aláwọ̀dúdú àkọ́kọ́, àti ṣoṣo titi dòní, ti yio kópa ninú Ijokopa àwọn ọ̀gá ọmọ-Ologun ile Amẹrika (Aint Chiefs of Staff).Igba Ewea bi Colin Luther Powell ni ọjọ́ 5 oṣù kẹrin ọdún 1937 ni Harlem tó jẹ́ àdúgbò kan ni Ilu New York fun Luther Theophilus Powell àti Maud adojú McṢóro ti wọn kọ wá sílẹ̀ lati ilẹ̀ Jàmáíkà..
wikipedia
yo
Apa awon obi re kan tun wa lati ile SkotNábótì ati ìrẹlánNA..
wikipedia
yo
Powell lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Morris High School tó fi ìgbà kan jẹ́ ti ìgboro ní Bronx, ó parí níbẹ̀ ní 1954.Iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀ ni ilé-iṣẹ́ ológunPowell darapọ̀ mọ́ Reserve Office' Training Corps ní ilé ẹ̀kọ́ City College ní New York ó sì ṣàlàyé rẹ̀ lẹ́yìn ìgbà ná gẹ́gẹ́ bí ìrírí tí ó mú inú rẹ̀ dùnjùlọ láyé rẹ̀, pé ohun ti rí ohun tí ohun fẹ́ràn tí òhun sì mọ̀ọ́ ṣe, lọ́kàn rẹ̀ pé “Ohun ti wá ara ọ̀hún rí.” Gẹ́gẹ́ bí kéde, Powell darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ àwọn ayìnbọn pershing ni City College..
wikipedia
yo
Nígbàtó parí ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní City College ní 1958, ó gba ipò gẹ́gẹ́ bí ìkẹ́ta ajagun ní ilé-iṣẹ́ ológun jagunjagun ilẹ̀ Amẹ́ríkà (Second Lieutenant, United States Army)..
wikipedia
yo
Nígbàtó parí iṣẹ́ ìgbìmọ̀ ọ̀rọ̀ abo ilẹ̀ Amẹ́ríkà, Powell gba ìgbésókè sí ipò ọ̀gágun lábẹ́ ààrẹ George H.W..
wikipedia
yo
bush, ó sì ṣiṣẹ́ nígbà díẹ̀ gẹ́gẹ́ bi alase, ilé-iṣẹ́ èṣe àwọn ológun jagunjagun ilẹ̀ Amẹ́ríkà, tó un mojuto gbogbo ológun jagunjagun, ológun jagunjagun alágbepamọ́, àti àwọn ẹyọ ilé-iṣẹ́ ológun àgbéjọ ilẹ̀ Amẹ́ríkà (u.S..
wikipedia
yo
National Guard) fún orílẹ̀ Amẹ́ríkà, Alaska, Hawaii àti Puerto Rico.Alaga Ijokopapo àwọn ọ̀gá ọmọ-ológun-se isẹ́ ológun tó ṣe gbeyin, láti October 1, 1989 titi di September 30, 1993 ni GẸ́GẸ́ BÍ alága ìkejìlá Ijokopapo àwọn ọ̀gá ọmọ-ológun, èyí ní ipò ológun tọ̀RI_*ní ilé-iṣẹ́ Alákè Oro-Abo Ilẹ̀ Amẹ́ríkà (U.S..
wikipedia
yo
of defense).ItỌ kika lẹ́kùnrẹ́rẹ́Powell, Colin A..
wikipedia
yo
And Joseph Perco, my American journey, Ballantine Books, 1995..
wikipedia
yo
òjìd-in ní olúìlú orile-ede Jemani.itọkasi àwọn ìpínlẹ̀ Jemaniàwọn oluilu ní Europe..
wikipedia
yo
ROMANIA jẹ́ orílẹ̀-èdè ní orílẹ̀ Europeìtọ́ka àwọn orílẹ̀-èdè Europe..
wikipedia
yo
Louis FarraKhan (ọjọ́ Louis Eugene Waltẹ́ńbẹ́lú; May 11, 1933) jẹ́ alákitiyan àti olórí ẹlẹ́sìn mùsùlùmí Nation of Islam ará Amẹ́ríkà.Ìtọ́kasíàwọn ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Angela Yvonne Davis (ibi, January 26, 1944 ní Birmingham, Alabama)àwọn ara Ameria ọmọ Afrika Amerikáá kan Adi ara Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Michaelle Jean (; Born September 6, 1957) jẹ́ Gómìnà àgbà orílẹ̀-èdè Kánádà.Ìtọ́kasí ara Kánádà..
wikipedia
yo
Klaus Ener (A bi ni 8 August, 1964) jẹ Olùkọ̀wé, akọewi ati Ayíedesédè Ara Obáàge.iwe Vermells; Setẹyọ Editorial, urus 2009, ISBN978-84-925-10-10-9 HOminidemini f' Verlag, Vienna 2008, ISBN978-3-3-13-99-7-4 auf der Ki. Arogernauth Verlag, Gosau, Gosau, ISBN978-3-3-25-47-67-5 lọ́sẹ̀; Edition Nonovey, Necken 2007, ISBN978-3 -85-197- gíga- Ìsọfúnni Complete English Version of This article.
wikipedia
yo
Àrùn Parkinson jẹ́ ààrùn ọ̀pọ̀lọ́ tí ó ní ṣe pẹ̀lú ẹ̀yà ọ̀pọ̀lọ́ tí ó rọ́mọ bí ènìyàn ṣe ń rìn..
wikipedia
yo
Ní ìbéèrè ààrùn yìí, òun tí a máa ń sábà rí ni kí ara máa gbọ̀n, kí ó máa le adé| kí ènìyàn má lè rìn dáradára..
wikipedia
yo
Ó wọ́pọ̀ láàrin àwọn okùnrin ju obìrin lọ.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Internet Hadlo Version 4 (IPv) ṣe ìtumọ̀ àẹ̀sì IP kan gẹ́gẹ́ bí nọmba oní 32-bit..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n, nítorí bí Internet ṣe ti tóbi tó àti ìdínkù àwọn Adiẹ̀sì IPv4 tó wà, ọ̀nà tuntun mìíràn fún IP (IPv6), tó un lo 128 bíts fún àẹ̀sì IP, jẹ́ ṣíṣe àjohùnsí ní ọdún 1998..
wikipedia
yo
Ìlọ IPv6 ti bẹ̀rẹ̀ láti àrin ìgbà ọdún 2000.Àwọn Adiẹ̀sì IP ún jẹ́ kíkó àti híhan ní ọ̀nà tó ṣe é rí ká fún ọmọ ènìyàn, fún àpẹrẹ, gẹ́gẹ́ bí nínú IPv4, àti nínú IPv6..
wikipedia
yo
Ìtóbi ìṣọ́nà ìfikúnwaju fun Adiẹ̀sì je yiyansile ninu CIDr notation nipa sise ìfikúnleyin Adiẹ̀sì pelu nọmba awon bit pataki, f.A., , to je ikannaa mo subNet Mask tí wón unlo lati ibere.Ìtọ́kasí Omonfiẹ̀sì ipinternet..
wikipedia
yo
Imọ ogbon jẹ ẹkọ lori imudaniloju ati àmújáde.itọkasi ìmòye..
wikipedia
yo
John Evans Fífii Atta Mills (21 July 1944 – 24 July 2012) jẹ́ Ààrẹ ilẹ̀ Ghana láti 2009 dé ìgbà ikú rẹ̀ ní 2012.Ìtọ́kasí àwọn olóṣèlú ará Ghana..
wikipedia
yo
RIRI LANKA tàbí olominira Toṣèlú Sosia Ilẹ̀ Sri láKA jẹ́ orílẹ̀-èdè ògésù ní gúúsù Asia.Ìtọ́kasí àwọn ìdálè-èdè — Asia..
wikipedia
yo
Alaṣẹ Ijoba Orilẹ-ede Palestine (palẹ̀Uts National Authority)Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Francis Arinze (ọjọ́ìbí 1 Oṣù Kọkànlá 1932) jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà láti ẹ̀yà Ìgbò tó jẹ́ Kardin ijó Katoliki ti Romu.Ìtọ́kasí sí Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ogun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejì tàbí Ogun Àgbáyé Kejì jẹ́ ogún tí ó pa gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè àgbáyé pọ̀ lẹ́ẹ̀kan-ṣoṣo tí ó bẹ ní àárín ọdún 1939 sí ọdún 1945..
wikipedia
yo
Ogun yi je eyi ti o kan gbogbo awon orile-ede agbaye ti won je alagbara ti won si laami-laaka..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n jagun náà ni a lè pín sí méjì..
wikipedia
yo
Awon apa kini ni ongbeja nigba ti awon apa keji je atoja..
wikipedia
yo
Iye awon ti won je jagun-jagun ti won kopa ninu ogun yi je ogbaorun un Milionu lati awon orile-ede ti won je ogbon Lapapọ..
wikipedia
yo
Àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n jẹ́ oníjà gan an sa ipá wọn nípa lílo gbogbo ọrọ̀-ajé, ìṣúná, ilé-iṣẹ́ jàǹkàn-jàǹkàn, iwadi ìmọ̀ sáyéensì ti wọ́n ní láti fi jagun náà, èyí kò jẹ́ kí á mọ nkan ogún àwọon ọmọ ogun nìkan ni àwọn orílẹ̀-èdè yí lọ láti fi jagun ni tàbí wọ́n lo àwọn nkan mìíràn tí kìí ṣe ti olóhun tí ó jẹ́ ti àwọn ará ìlú lásán..
wikipedia
yo
Ogun Àgbáyé ẹlẹ́kejì yí jẹ́ ọ̀kan gbòógì nínú àwọn ògùn tí èmi àti dúkìá ti ṣòfò jùlọ lágbàáyé nínú ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ ọmọ adáríhurun..
wikipedia
yo
Àwọn ológun tí wọ́n sọ ẹ̀mí wọn nù níbi ìjà-àgbà yí jẹ́ mílíọ̀nù ọ̀nà àádọ́rin àti mílíọ̀nù lọ́nà márùndínláàdọ́taỌ̀sán án ènìyàn, nígbà tí àwọn tí wọ́n kù jùlọ jẹ́ ará ìlú lásán tí wọ́n kìí ṣe jagun-jagun..
wikipedia
yo
Ohun tí ó fàá tí òkú yí fi pọ̀ tó bẹ́ẹ̀ ni ìwà ìmọ̀-ọmọṣekú pa ọ̀pọ̀ ènìyàn tí àwọn Gẹ̀ẹ́sì ń pè ní jẹnosáítì, nípa ìlànà ìfẹ́bí , pípa àwọn aláìṣẹ̀ àti fífi àjàkálẹ̀ àrùn pani..
wikipedia
yo
Wọ́n ṣàmúlò àwọn bàlúù dìgbòjàjà nínú Ogun Àgbáyé yí, bá kàn náà ni wọ́n tún lọ àwọn àdó olóró tí ó le pa ìlú run, bẹ́ẹ̀ sì ni wọ́n tún lọ jíclear l8Cláti jagun lásìkò náà., lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé àdéhùn àti òfin oríṣiríṣibí ó ṣe bérí gbo Ogun Ogun Àgbáyé yí bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kínní Oṣù Kẹ́san án ọdún 1939, nígbà tí orílẹ̀-èdè ilé-iṣẹ́ ológun Nazi ti ilẹ̀ Germany kọlu orílẹ̀-èdè pódìgírì ti àjọ ìṣọ̀kan United Kingdom àti orílẹ̀-èdè Faransé náà sì ṣígun kọlu orílẹ̀-èdè Germany lẹ́ni tí ó ń gbèjà orílẹ̀-èdè pólándì ní ọjọ́ kẹta tí Germany kọlù pólándì..
wikipedia
yo
Níparí ọdún 1939 sí 1941, orílẹ̀-èdè Germany tí ń ṣàkóso lórí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ilẹ̀ àti ìlú ní apá Yúróòpù, lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìfowóbọ̀wé àdéhùn àti òfin oríṣiríṣi..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn èyí, orílẹ̀-èdè Germany, orílẹ̀-èdè Japan ati orílẹ̀-èdè Italy kórapo di ọkan tí wọ́n pe orúkọ wọn ní Axis Alliance, nígbà tí àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn náà ṣì ń dara pọ̀ mọ́ wọn nígbà tí ó yá..
wikipedia
yo
Nínú wé àdéhùn tí ọ̀gágun mọ̀lọ́tọ̀v-Ribbekun fowobo ní ní oṣù kẹlú ọdún 1939, orílẹ̀-èdè Germany àti Soviet Union nígbà náà fowó-sowọ́pọ̀ láti túbọ̀ gba àwọn ilé àwọn alámùúlégbè wọn ní Yúróòpù síwájú sí.Àkíyèsí footnotesáwọn ìtọ́kasí Àwọn ogun..
wikipedia
yo
Zadie Smith (born on 25 October 1975) jẹ́ Olùkọ̀wé Ìtàn Àròsọ ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sìpọ̀àwọn Olùkọ̀wé Àrà Britani..
wikipedia
yo
Philip KinṢàpèjúwe Dick (December 16, 1928 – March 2, 1982) jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Amẹ́ríkà Olukọwe Arosọ ati Arosọ Sayẹnsi Ojodélé Olukọwe Ara Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Eré òmìnira tàbí òmìnira níyí ayé (Statue of lberty) àwọn ibi ọ̀ṣọ́ àgbáyé..
wikipedia
yo
Ògòǹgò (Strut camelus) jẹ ẹyẹ to tobi ṣugbọn ti ko le fo ti won je abinibi si Afrika.Ìtọ́kasí awọn eye..
wikipedia
yo