cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Bakanna, o tun gba ipo kinni ni emerin fun awọn idije inuulé, ohun si tun ni adijekinni Marathon idaji agbaye 2001..
wikipedia
yo
Ní Oṣù kọkànlá Ọdún 2021, Haile GbreSela wà ní iwájú Ògùn ní Etiopia lòdì sí àwọn ọlọ̀tẹ̀ ti TiGray.Ìtọ́kasí Ara Ethitọ́kaìtọ́júàwọn tó gba èso Wúrà Wúrà fún Ethiópíà..
wikipedia
yo
Àwọn ìbejì jẹ́ àwọn ọmọ méjì tí ìyá wọn lóyún papọ̀, wọ́n lè jẹ́ obìnrin méjì, ọkùnrin méjì tàbí ọkùnrin kan àti obìnrin kan..
wikipedia
yo
Àwọn ìbejì lè tì àti inú ẹ̀yin kan jáde tàbí láti inú ẹ̀yin ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀..
wikipedia
yo
Àwọn tí ó jáde láti inú ẹ̀yin kan ma ń jó ara wọn, wọ́n sì ma ń jẹ́ ọkùnrin méjì tàbí obìnrin méjì..
wikipedia
yo
Ní ìgbàìgbà(ìṣẹ̀lẹ̀ yí kò wọ́pọ̀), àwọn ìbejì kan lé ní bàbá méjì ọ̀tọ̀Stata ní gbogbo àgbáyé, ẹ̀yà Yorùbá ni àwọn ọmọ wọn ń ya ìbejì jù, àwọn ìbè 45 sí 50(àwọn ọmọ 90 sí 100) ni ó ń ya ibeji nínú gbogbo ọmọ ẹgbẹ̀rún tí wọ́n bá bí bí ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Muhammad Anwar Al ṣàdát (25 December, 1918 – 6 October, 1981) jẹ́ olóṣèlú àti Ààrẹ ilẹ̀ Egypti láti 5 October, 1970 títí dé 6 October, 1981.Àwọn ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1918àwọn ọjọ́aláìsí ní 1981àwọn ara Egypt..
wikipedia
yo
ìrẹ́lándi àpawáfo jẹ́ orílẹ̀-èdè ní ìṣọ̀kan Ilẹ̀-Ọba tó fihá sí ìlà-Ariwa Erékùṣù Kadisan..
wikipedia
yo
Ẹ̀sìn Krístì tàbí ìsìn Krístì tàbí ẹ̀sìn onígbàgbọ́ (ti àwọn míràn máa ń pè ní ẹ̀sìn kiriyó) jẹ́ ẹ̀sìn Ọlọ́runkan tó dá l'órí ìgbésíayé àti àwọn ẹ̀kọ́ Jésù ti Nasareti gẹ́gẹ́ bí wọ́n ṣe kọ̀sílẹ̀ nínú Májẹ̀mú Tuntun ti Bíbélì.Ẹ̀sìn ìgbàgbọ́ ló fẹ́rẹ̀ tàn kálẹ̀ jù ní gbogbo àgbáyé..
wikipedia
yo
Ní bíi nkan an ọdún bíi mẹ́wá sẹ́yìn iye àwọn tí ó ń ṣe ẹ̀sìn ìgbàgbọ́ ní àgbáyé fẹ́rẹ̀ tó bílíọ́nù méjì ènìyàn bíi àwọn ẹ̀sìn míràn ẹ̀sìn ìgbàgbọ́ ní àwọn ọ̀pọ̀ ìgbàgbọ́ àti àṣà tí ó dìrọ̀ mọ́..
wikipedia
yo
Fún àwọn tó bá jẹ́ onigbagbọ nìkan ló lè ní òye ìtumọ̀ àwọn òpó igbagbọ ti ẹ̀sìn yí dìrọ̀ mọ́ dáradára..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n síbẹ̀síbẹ̀ a sì lè ṣàlàyé fún aláìgbàgbọ́ nínú ẹ̀sìn ìgbàgbọ́ ohun tí ẹ̀sìn ìgbàgbọ́ jẹ́.
wikipedia
yo
A lè rí ẹ̀sìn ìgbàgbọ́ gẹ́gẹ́ bí àpéjọpọ̀ àwọn onígbàgbọ́..
wikipedia
yo
A tún lè ríi gẹ́gẹ́ bí ìgbésíayé ayé tí onílọ́pọ̀ ń gbé..
wikipedia
yo
A lè rí ẹ̀sìn igbagbọ gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ìsìn, a tún lè ríi gẹ́gẹ́ bíi àṣà, gbogbo ìtumọ̀ yìí tabi jù bẹ́ẹ̀ lọ ni a lè fún ẹ̀sìn igbagbọ..
wikipedia
yo
A lè ṣe afiwe ẹ̀sìn igbagbọ pẹlu awọn ẹsin miran latari pe ọpọlọpọ ẹsin lo ni awọn abuda ti ẹsin igbagbọ ni..
wikipedia
yo
Fún ìdí èyí yó sàǹfàní nígbà tí a bá ń sọ nípa ẹ̀sìn ìgbàgbọ́ láti máa mẹ́nu ba àwọn ẹ̀sìn míràn..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n ó ṣe pàtàkì náà láti ṣàgbéyẹ̀wò àwọn àbùdá tí ó jẹ́ ti ẹ̀sìn ìgbàgbọ́ ohun pàtàkì tí ó jẹ́ àárín gbùngbùn ẹ̀sìn ìgbàgbọ́ tí ó dàbí ọ̀pọ̀ ti ohun gbogbo dìrọ̀ mọ́ ni Jesu ..
wikipedia
yo
Ìgbàgbọ́ nínú ohun tí Jesu jẹ́ tàbí tí ó ṣe nígbà ayé rẹ̀ ló bí ìlànà tàbí ẹ̀kọ́ tí ìjọ kọ̀ọ̀kan ń tẹ̀ lé nínú ẹ̀sìn ìgbàgbọ́..
wikipedia
yo
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ọpọlọpọ onigbagbọ ló gbàgbọ́ pé eniyan ìyanu ni Jesu, ati pé ìṣẹ̀dá rẹ̀ yàtọ̀ sí ti ẹ̀dá alàyè yókù wọn á (àwọn onigbagbọ) sì tún máa kọ́ni láti tẹ̀lé àwọn ìkọ́ni Jesu, sibẹsibẹ, ìmọ̀ àwọn onigbagbọ nípa ohun tí Jesu jẹ́ nítòótọ́ kò jọra wọn..
wikipedia
yo
Nítorí ìdí èyí yó ṣe pàtàkì fún wa láti lo Bíbélì Ìwé Mímọ́ àwọn onígbgagbọ́ láti ṣe atọ́nà wa nínú àlàyé yìí..
wikipedia
yo
Bíbélì jẹ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọrun tí a ti ọwọ́ àwọn eniyan mímọ́ kọ..
wikipedia
yo
Apá kan jẹ́ májẹ̀mú láíláí tí a ti ọwọ́ àwọn wòlíì kọ nígbàtí májẹ̀mú Titun jẹ́ èyí tí a ti ọwọ́ àwọn Àpósítélì kọ́ nípa Jésù láti fi tan ìwàásù Jésù kálẹ̀..
wikipedia
yo
Àwọn ẹlẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì tí a ń pè ní (‘‘ gbà pé májẹ̀mú láíláí wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú májẹ̀mú Titun..
wikipedia
yo
Májẹ̀mú laìmu sọ nípa iṣẹ́ ìgbàlà tí Jésù wá ṣe nílé ayé..
wikipedia
yo
Èyí ni láti sọ pé ẹlẹ́ṣẹ̀ ni gbogbo ọmọ adarí ìlànàú..
wikipedia
yo
Àlàyé ìbẹ̀rẹ̀ ìran ọmọ ènìyàn wà nínú Jẹ́nẹ́sísì (Genesis)..
wikipedia
yo
Jesu ṣe ọpọlọpọ iṣẹ́ ìyanu láti fi ìfẹ́ Olodumare hàn sí àwọn ọmọ eniyan..
wikipedia
yo
Onírúurú ìjọ onigbagbọ ló ní oríṣìíríṣìí ìtumọ̀ fún Bíbélì torí ìdí èyí onírurú ìlànà ẹ̀sìn ní ìjọ kọ̀ọ̀kan ní..
wikipedia
yo
ati pé igbagbọ wọn nípa ohun tí Jesu jẹ́ yàtọ̀ díẹ̀díẹ̀ sibẹsibẹ gbogbo wọn gbà pé Olùgbàlà ni Jesu..
wikipedia
yo
Àwọn onígbàgbọ́ míràn kò faramọ́ èyí torí kò ṣeé fòye gbé bí ènìyàn tàbí ẹ̀dá mẹ́ta ṣe lè parapọ̀ di ọ̀kan..
wikipedia
yo
Àmọ́ ṣá ọpọlọpọ ìjọ àwọn onigbagbọ lọ gbàgbọ́ ninu àwọn opó maraarun tí a là sílẹ̀.
wikipedia
yo
ìtànkálẹ̀ ẹ̀sìn igbagbọ ní ìlú Jerusalẹmu ni ẹ̀sìn igbagbọ ti bẹ̀rẹ̀ kó tó di pé àwọn ọmọ ogun Róòmù ba ìlú náà jẹ́ ní ọgọrin ọdún lẹ́yìn ikú Jesu..
wikipedia
yo
Díẹ̀ nínú àwọn Júù ló kọ́kọ́ di onígbàgbọ́ torí wọ́n gbà pé Jésù Kírísítì ni àmúṣẹ àsọtẹ́lẹ̀ àwọn Wòlíì nínú Májẹ̀mú láíláí ṣùgbọ́n láti ipasẹ̀ iṣẹ́ ìwàásù tí Pọ́ọ̀lù Apoisitélì ṣe ní orílẹ̀èdè àwọn kènfèrí(àwọn aláìgbàgbọ́), ọ̀pọ̀lọpọ̀ kènfèrí bẹ̀rẹ̀ sí ní dìde inúnibíni jẹ́ bíi ọmọ ìyá awùsá fún ẹ̀sìn ni kò sí ẹ̀sìn kan tí kò ní alátakò..
wikipedia
yo
Bí ẹnìkan kò bá gba ohun tí mo gbàgbọ́ ó ṣeéṣe fún irú ẹni bẹ́ẹ̀ láti takò mí..
wikipedia
yo
Bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ló ṣe rí fún ẹ̀sìn ìgbàgbọ́, onírúurú àtakò ṣùgbọ́n èyí tó burú jù ní inúnibíni láti ọ̀dọ̀ ọba Nero tí í ṣe Olórí ìjọba Róòmù nígbànã ọba yìí kò lè gbà kí ẹnìkan máà pe Jesu ní Olúwa nígbà tí òun sì jẹ Ọba, ìdí nìyí tí ó ṣe gbógun ti ìgbàgbọ́..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n lẹ́yìn ọba yìí, ọba kan jẹ́ tí ó ń jẹ́ Constantine..
wikipedia
yo
Èyí mú kí ẹ̀sìn igbagbọ gbayì nígbà náà ó sì wá rọrùn fún ẹnikẹ́ni láti di onigbagbọ..
wikipedia
yo
Bákannáà eléyìí mú kí ìgbàgbọ́ di yẹpẹrẹ, kó di gbẹ̀fẹ́, yàtọ̀ sí èyí Ìjọ páádi(Catholic) tó wà ní Róòmù nkó àwọn èèyàn ní pápá mọ́ra wọ́n fi Jùjú bọ́ àwọn ènìyàn lójú wọn gbé ọ̀rọ̀ àṣà ayé wọ inú ìjọ..
wikipedia
yo
Eléyìí sì mú kí èdè àìyedè àti ìṣọ̀tẹ̀ bẹ̀rẹ̀ nínú ìjọ..
wikipedia
yo
Ìgbà tó ya ìyapa bẹ̀rẹ̀ sí ní dé àwọn èèyàn tí ó sì sokunfa ìyapa náà ní àwọn èèyàn bíi Martin Luther, John Calvin, Ernst Troeltsch àti àwọn ènìyàn míràn tí a kòle dárúkọ..
wikipedia
yo
Wọ́n tako àwọn àṣà bíi kí á máa ṣe ìtẹ̀bọmi fún ọmọdé, ẹ̀kọ́ lórí mẹ́talọ́kan àṣepọ̀ ìjọ àti ìjọba, ṣíṣọ́ àwọn olórí ẹ̀sìn bíi ti Ọlọ́run..
wikipedia
yo
Ìyapa ti o ṣẹlẹ kuro ninu Ijo páádi (Catholic) lo bi awọn ijo bii onítẹ̀bọmi (Baptist), Àgùdà (Anglican), Methodist ati bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ọ̀pọ̀lọpọ̀ onírúurú àjọ àti ìpàdé ni wọ́n gbé kalẹ̀ láti ṣe àtúnṣe àwọn àṣà ìjọ, síbẹ̀ ọrọ̀ kò ní ojú Itu..
wikipedia
yo
Yàtò sí èyí ìtànkálẹ̀ ẹ̀sìn ìmàle (Islam) tún ṣàkóbá fún ẹ̀sìn igbàgbọ́ lọ́pọ̀lọpọ̀, ìdàgbà sókè ẹ̀sìn ìmàle bèrè ní ọgọ́ọ̀rùn – ún mẹ́fà ọdún lẹ́yìn ikú Jésù..
wikipedia
yo
àmọ̀sá láyé òde òní kí ẹ̀sìn ìgbàgbọ́ má baà sọ òtítọ́ rẹ nù onírúurú ìgbìmọ̀ àti àjọ láti gbé kalẹ̀ láti mú àjọṣepọ̀ àti àsọyépọ̀ wá láàrín àwọn ìjọ..
wikipedia
yo
Pẹlupẹlu oniruuru ijo Lọti n gbiyanju lati ṣe iwadii ijinle sinu Bibeli lati lóyè ohun ti Bibeli n so..
wikipedia
yo
Kùránì jẹ́ ìwé mímọ́ ẹ̀sìn Islámì Al-́2 (Kùránì) Al qura·an Adpopo pẹ̀lú Ìtúmọ̀ rẹ̀ ní Èdè Yorùbá..
wikipedia
yo
(May 3, 1933– December 25, 2006) je olorin omo ile Amerika.Awon itọkasi awon omo ​ Amerisee ara Amerika ara Amerika..
wikipedia
yo
Thomas Yabe boni (ọjọ́ 1 July 1952) jẹ́ gbajúmọ̀ onímọ̀ ìfowópamọ́ àti òṣèlú àti Ààrẹ orílẹ̀-èdè Benin láti ọdún 2006 sí 2016..
wikipedia
yo
O gba ijoba leyin ti o wole ninu idibo Aare ti orile-ede Benin lodun 2006..
wikipedia
yo
Bẹ́ẹ̀ náà, lọ́tùn wọlẹ̀ lẹ́ẹ̀kan si lọ́dún nínú ìdìbò Ààrẹ orílẹ̀-èdè náà lọ́dún 2011..
wikipedia
yo
Ní àkókò yìí, òun ni wọ́n yàn gẹ́gẹ́ bí alága Àjọ Àwọn Orílẹ̀-èdè Adúláwọ̀, African Union láti ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù kìíní ọdún 2012 sí ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù kìíní ọdún 2013.Ní oṣù kẹsan ọdún 2021, Patrice Talon ati Thomas Boni Yyí, tí wọ́n jẹ́ ọ̀rẹ́ kòríkòsùn olóṣèlú kẹ̀yìn sí ara wọn, tí wọ́n sì di ọ̀tá nítorí òṣèlú..
wikipedia
yo
Nígbà kan tí wọ́n pàdé nínú ààfin Marina ní Cotonou láti jíròrò ìtẹ̀síwájú ìlú wọn, ìmọ̀ wọn kò jó rárá lórí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ètò ìṣèjọba, pàápàá jùlọ ọ̀rọ̀ lórí ìtúsílẹ̀ àwọn òṣèlú tí wọ́n wà lẹ́wọ̀n.Ìgbésí ayé rẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀ àti iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣìṣẹ́ ilé-ìfowópamọ́wọ́n bí Thomas Boni Yyí ní agbègbè TchaOurou, ní Ìjọba-ìbílẹ̀ Borgọ́ Department lápá ìlà-oòrùn orílẹ̀ èdè Benin, tí a mọ̀ nígbà kan rí ní orílẹ̀ èdè Dahomey..
wikipedia
yo
Ó bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ rẹ̀ olú-ìlú agbègbè náà, Parakou kí ó tó tẹ̀síwajú láti kàwé gboyè Ikeji nínú ìmọ̀ ètò ọ̀rọ̀-ajé ní National University of Benin..
wikipedia
yo
Ó tẹ̀síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ láti tún kàwé gboyè kejì òmíràn nínú ìmọ̀ ìmọ̀ ètò ọ̀rọ̀-ajé bákan náà ní Cheikh anta Diop University ní Dakar, lórílẹ̀ èdè Senegal, ó kàwé gboyè dókítà nínú ìmọ̀ ètò ọrọ̀-ajé àti òṣèlú ní University of Orléans, lórílẹ̀-èdè France àti ní Paris Dauphiné University lọ́dún 1976.Lẹ́yìn ẹ̀kọ́ rẹ̀, bóbónì ṣiṣẹ́ nílé ìfowópamọ́ fún ìgbà pípẹ́..
wikipedia
yo
Láti ọdún 1975 sí 1979, ó ṣiṣẹ́ ní Benin Commercial Bank kí ó tó dara pọ̀ mọ́ Central Bank of West African States (BCBCA) gẹ́gẹ́ bi òṣìṣẹ́ láti ọdún 1977 sí 1989..
wikipedia
yo
Láti ọdún 1992 sí 1994, ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí olùgbaninímọ̀ràn sí ààrẹ orílẹ̀ èdè Benin lásìkò náà, Nicephore Yglo..
wikipedia
yo
Lọ́dún 1994, ó fi ipò náà sílẹ̀ láti di Ààrẹ ilé-ìfowópamọ́ West African Development Bank (Bóad).Ó bẹ̀rẹ̀ ìjọba rẹ̀ ní ọjọ́ kẹfà oṣù kẹrin ọdún 2006..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀ ènìyàn ni wọ́n tú yáyá tu yáyá nínú ìdìbò náà tí gbogbo ènìyàn gbà pé kò sí àbòsí nínú rẹ̀.Àwọn ìtọ́kasíàwọn ará Benin..
wikipedia
yo
Babatunde Raji Fashola (ti a bi ni 28 June, 1963) je agbejoro ati oloselu orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
Ó ti fìgbà kan jẹ́ Gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó fún sáà méjì láti ọdún 2007 sí ọdún 2015 lábẹ́ àsíá ẹgbẹ́-òṣèlú All Progressives Congress..
wikipedia
yo
Oloye Bola Tinubu ni o je gomina ipinle Eko ṣaaju rẹ..
wikipedia
yo
lọ́dún 2015, Ààrẹ Muhammadu Buhari yán-án gẹ́gẹ́ bí Mínísítà fún Ètò Iná-mọ́ná, Ilé Ìgbẹ́, àti iṣẹ́..
wikipedia
yo
Ààrẹ tún tún-un yàn lọ́dún 2019 sí ipò yìí kan náàsí ipò Mínísítà fún Agbára àti Iná Amọnaìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ a bí Fashola ní ọjọ́ 28 June, ọdún 1963, ní Ìpínlẹ̀ Èkó, ní Island Maternity Hospital, sínú ìdílé Ademola Fashola, tó fìgbà kan jẹ́ akọ̀ròyìn fún ìwé-ìròyìn Daily Times ti Nàìjíríà, àti OlùFunke Agúnbíadé, tó jẹ́ nọ́ọ̀sì.Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi Amofí-ẹjọ́-ẹjọ́ gíga wọn pè é sí ilé-ẹjọ́ gẹ́gẹ́ bíi agbẹjọ́rò àti onídùúró ti ilé-ẹjọ́ gíga ní November 1988 lẹ́yìn tó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní Nigerian Law School, ní Ìpínlẹ̀ Èkó láàárín ọdún 1987 àti 1988.Àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀ Fashola, tó jẹ́ ènìyàn kan tó gbajúmọ̀ ní ilé-ẹjọ́ gíga ilẹ̀ Nàìjíríà, ti gba àmì-ẹ̀yẹ àti ìwé-ẹ̀rí títayọ bíi Distin alumnus aluw tí Ìgbìmọ̀ Àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ gboyè ti Yunifásítì ìlú Benin fún un..
wikipedia
yo
O tun gba ami-eye ti Lagos State Public Service Club Pasasi Award fun ise TÍTAYỌ re si idagbasoke..
wikipedia
yo
Bẹ́ẹ̀ náà ni ti Alliance for Democracy, “ami-ẹyẹ ti ijọba ibilẹ igbogbo Báku” ni ibamu pẹlu ifarahan ati iṣẹ rẹ si ẹgbẹ naa.Babatunde Fashola tun jẹ ALÁBÒÓJÚTÓ awọn akekoo imọ-ofin, ti Yunifasiti Ilu Benin, oun si ni akekoo keji to máa kẹkọọ nipa imọ-ofin ni Yunifasiti Ilu Benin, ati ọmọ ẹgbẹ Nigerian Law School akọkọ to kẹkọọ gboye ni ọdun 1988, ti wọn fi joye Senior Advo of Nigeria..
wikipedia
yo
Fashola naa ni Chief of Staff akoko to gba iru oye bẹẹ..
wikipedia
yo
Babatunde Fashola je omo-egbe Nigerian Bar Association, International Bar Association ati Chartered Institute of Taxation of Nigeria.Ni osu kewaa odun 2022, oye nla ti orile-ede Naijiria kan ti a mo si oye commander of the order of the Niger (CON) ni a tun fi da a lola lati owo Aare Muhammadu Buhari.Awon itọkasiawon gomina ipinle Eko..
wikipedia
yo
Bola Ahmed Tinubu (ojo ibi ojo kàndínlọ́gbọ̀n osu keta, odun 1952) je Aare orile-ede Nigeria ti won se ibura fun lọjọ kokandinlogbon osu karun-un odun 2023 leyin ti o jawe olubori ninu idibo Aare odun 2023..
wikipedia
yo
O jẹ Gomina-ana ipinle Eko laarin odun 29 May odun 1999 titi di odun 29 May, 2007..
wikipedia
yo
Awon ara ilu ti koko dibo yan Bola Ahmed Tinubu lati di gbeyin ni odun 1992, amo won fagile ibo naa ni odun (12 June, 1993)kíkéde ete lati dupo àárẹ̀ni ojo Kọkànlá, osu kini, odun 2022(January 11, 2022), Bola Ahmed kede ete re lati dupo Aare Naijiria ni odun 2023 labẹ egbe oselu All Progressives Congress(APC)..
wikipedia
yo
Ni ojo kejo osu kefa odun 2022, Tinubu jawe olubori ninu idibo-irin Aare ninu egbe oselu All Progressive Congress(APC) pelu ami ayo 1271, lati bori igbakeji Aare Yemi Osinbajo ati Rotimi Amaechi ti o gba 235(Osinbajo) ati 316(Rotimi).Awon itọkasiawon gomina ipinle Ekoawon ara Naijiriàwọn eniyan alààyè..
wikipedia
yo
Chief Saheed Túkugbobo Fawehinmi, ni Séríkí Mùsùlùmí ti Òndó, jẹ́.Àwọn àmì ẹ̀yẹ ní ọjọ́ Kọkànlá oṣù kẹfà ọdún 1993 a fún Fawehinmi ní Ẹ̀bùn Bruno KreisKY..
wikipedia
yo
Ẹ̀bùn yìí, tí a dárúkọ ní ọ̀la tí Bruno Kreissky, ni a máa ń fún àwọn èèyàn àgbáyé tí ó ní ìlọsíwájú àwọn ìdí ẹ̀tọ́ ènìyàn..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1998, ó gba ààmì ẹ̀yẹ Bernard Simmons ti International Bar Association ní ìdánimọ̀ ti àwọn ètò ènìyàn àti iṣẹ́ Ìjọba tiwantiwa..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2018, Olóyè Fawehinmi ni a fún ní àṣẹ orílẹ̀-èdè Niger lẹ́hìn ikú rẹ̀, ọlá kejì ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ikú rẹ̀ Fawehinmi kú ní àwọn wákàtí ìbẹ̀rẹ̀ ti ọjọ́ karùn-ún oṣù kẹsàn-án ọdún 2009 lẹ́hìn Ogun Pípẹ́ pẹ̀lú Akàn Aẹ̀dọ̀fóró..
wikipedia
yo
Wọ́n sìnkú rẹ̀ ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù kẹsàn-án ọdún 2009 sí ìlú rẹ̀ ní ilẹ̀ Òndó ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Fawehinmi kú ní sí ìbànújẹ́, nítorí ipò ti orílẹ̀-èdè rẹ̀ nígbà ikú rẹ̀, kò gba ọlá tí ó ga jùlọ tí orílẹ̀-èdè rẹ̀ fi fún un lórí ibùsùn ikú rẹ̀.Ìjà àmì-ẹ̀yẹ ti ìjọba orílẹ̀-èdè ní ọdún 2008 Fawehinmi kọ ọ̀kan nínú àwọn ọlá orílẹ̀-èdè tí ó ga jùlọ ti ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lé fún ọmọ ìlú kan - Order of the Federal Republic (OFR) – ní ìlòdì sí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún àìṣedéédé ìjọba láti ìgbà òmìnira Nàìjíríà.Ọgbà Gani Fawehinmi iwosan Ìwòsàn Gani Fawehinmi Health Diagnostic Center Òndó City.Àwọn àgbẹ̀rọ̀rọ̀ àgbà ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Augustus Taiwo "Tail" Sorin (Ọjọ́ìbí 20, 1922 – 27, 1994, 1994) jẹ́ olùjokọ́ àti Olùkọ̀wé Ọmọ-èdè Nàìjíríà.Àwọn Ọjọ́ìbí ni 1922 ní 1994–Àwọn ara Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ìtàn fi yé wa wípé ibi tí ó di ìlú Ìbàdàn l'óde òní bẹ̀rẹ̀ ní ọdún 1829..
wikipedia
yo
ní àkokò yí, ìrúkèrúdò pọ̀ ní gbogbo ilẹ̀ Yorùbá káàkiri, èyí ni ó sì fa ti jagunjagun tí a n pè ní lagélù fi wá tẹ̀dó sí ìlú Ìbàdàn..
wikipedia
yo
Èròǹgbà lagẹ́lù ni láti fi ṣe ibùdó fún àwọn jagunjagun.Ìtọ́kasíYorùbá..
wikipedia
yo
Indpu (pípè ), fún oníbiṣẹ́ bi ORÍLẸ̀-èdè OLÓMÌNIRA ilẹ̀ Finlándi, jẹ́ orílẹ̀-èdè Nordik kan tó bùdó sí agbègbè Fennosdia ní àpawaú Europe..
wikipedia
yo
O ni BO DE mọ́ SWEDEN ní ìwọ̀òrùn, Norway ní àríwá àti Russia ní Ilaọrun, Be Sínì Estonia wà ní gúúsù rẹ̀ nísí Ìkún-Omi Inlándi.Ìtọ́kasí àwọn orílẹ̀-èdè Europe..
wikipedia
yo
irak tabi orile-ede olominira Ile irakitọ́kasí Àwọn Orílẹ̀-Èdè Asia..
wikipedia
yo
Ebori Hussein ABD Al-Majid Al-tikriti (April 28, 1937 – December 30, 2006) ni Ààrẹ ilé irak láti July 16, 1979 títí dé April 9, 2003.Ìtọ́kasí.Àwọn Ènìyàn ara irak..
wikipedia
yo
Samuel Oluyemisí Fako CFR (Ojo Ojo kokanlelogun Oṣu Ọ̀wàrà, Ọdun 1938)..
wikipedia
yo
Ti a mọ̀ si olù faláé, jẹ́ òṣìṣẹ́ iléeṣẹ́ – ìfowópamọ́, alákòóso àti olóṣèlú lati Àkúrẹ́, ìpínlẹ̀ Ondó..
wikipedia
yo
Akọ̀wé ìjọba Ológun BIGIG ni lọ́dún January 1986 sí December 1990 ó sì jẹ́ Mínísítà Goba fún àsìkò ránpẹ́ ní ọdún 1990..
wikipedia
yo
O dije dupo Aare orilẹ-ede Naijiria ni ijọba olominira elekèéta ati ẹlẹ́ẹ̀kẹ́rin.igbẹ ayé ati ètò ẹ̀kọ́ rẹwọn bi falae sinu idile Oloye Joshua Alekete ati Abigail Àìná falae ni ojo kokanlelogun oṣu ọ̀wàrà, ọdún 1938 ni Ilu Abo, Àkúrẹ́..
wikipedia
yo
Ọmọ ilú Ondó ni Joshua fàláé ṣùgbọ́n tori àwọn àǹfààní tó wà ninú Àgbẹ̀ kókó, ẹbi faláé àti díẹ̀ lára àwọn ọmọ Àkúrẹ́ kò lọ si Ẹkùn kan tó súnmọ́ ti wọn pè ni àgọ́-àbọ̀ ti a tún mọ si ilú àbọ̀ nibi ti wọn tẹ̀dó si bíi olùdásílẹ̀..
wikipedia
yo
Ìlú ìgbárá-òkè ni wọ́n ti bí àti tó iyá fàláé ó sì kú lásìkò tó ń bímọ ní ọdún 1946 nígbà tí fàláé jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́jọ péré..
wikipedia
yo
Ìyá bàbá rẹ̀ ni (Olóyè Ọ̀sanyintùké fàláé – (ọmọ Adedipe) ti ó jẹ́ ọmọọmọ ìyá Deji ti Àkúrẹ́ àti ọmọ Elemọ ti Àkúrẹ́, Olóyè Adégbọ̀n Òpóẹyọ àtòsin (oun fúnra rẹ ọmọ-ọmọ Déjì Arakalẹ̀ ti Àkúrẹ́, Bàbá Òṣùpá)..
wikipedia
yo
Faláé lọ si Ile - ẹkọ alakobeere Anglican ni ilu Àkúrẹ́ nibi ti o pade iyawo rẹ ti o fẹ Rachel Ọlásùnlá Sshorántí, aburo olori afẹ̀nífẹ́ré Reuben Saberántí..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí ó parí ẹ̀kọ́ àkọ́bẹ̀rẹ̀, ó ṣe ìdánwò láti wọlé sí kọ́lẹ́jì Igbobi, wón sì gbà á wọlé ní ọdún 1953..
wikipedia
yo
Nigba ti o kẹkọọ gboye ni Igbobi, o lo pari eko re ni kọlẹji ijoba, Ibadan nni ọdun 1958 fun iwe eri giga ile - eko..
wikipedia
yo
Ó padà di olùkọ́ ni ilé-ẹ̀kọ́ girama ọyẹ́mẹ́kùn, Àkúrẹ́..
wikipedia
yo
O lọ si Yunifasiti Ibadan o si kẹkọọ gboye ninu Ẹkọ Oro -aje (Economics)..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn náà ó lọ sí Yunifásítì Yale ní ìlú Amẹ́ríkà ..
wikipedia
yo