cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Okòwò ilẹ̀ Nàìjíríà jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn èyí tó ń dàgbà kíákíá jùlọ lágbàáyé pẹ̀lú IMf tó ń gbèrò ìdàgbàsókè 9% fún 2008 àti 8.3% fún 2009..
wikipedia
yo
Ni ibere awon odun 2000 soke, sise awon omo Naijiria gbe pelu iye to din ni US$ 1.25 (PPPP) lojumọ..
wikipedia
yo
Nàìjíríà ni okòwò rẹ̀ tóbi jùlọ ní Áfíríkà, àti alágbára ní agbègbè ìwọ̀òrùn Áfíríkà.Tan ìsẹ̀rún àwọn ara NOK ní àárín Nàìjíríà ṣe eré gbígbẹ́ alámọ̀ tí àwọn onímọ̀ ayéèlú ti wárí..
wikipedia
yo
Eré Nok tó wà ní Minneapolis Institute of Arts, júwe ẹ̀ ẹni pàtàkì kan mú “ọ̀pá ìdaran” dání ní ọwọ́ ọ̀tún àti igi ní ọwọ́ òsì..
wikipedia
yo
Ìwọ̀nyí ni àmì-ìdámọ̀ aláṣẹ tó jẹ́ bíbápọ̀ mọ́ àwọn Farao ilé Egypti ayéejòun àti òrìṣà, Osiris, èyí ló ń sọ pé irú àwùjọ, ìdímúlẹ̀, bóyá àti ẹ̀sìn ilé Egypti ayéijọ́un wà ní agbègbè ibi tí Nàìjíríà wà lónìí ní ìgbà àwọn Farao..
wikipedia
yo
Ní apá àríwá, Kano àti Akinrọ́ ní ìtàn àkọsílẹ̀ tí ọjọ́ wọ́n dẹ̀yìn tó bí ọdún bẹ̃g K..
wikipedia
yo
Ní ìtẹ̀síwájú pẹ̀lú u òfin òkèèrè tó so mọ́ Áfríkà, Nàìjíríà mú àbá wá fún níná òwò kan náà ní ìwọ̀ìwọ̀ Áfríkà tí a máa jẹ́ Ríyín lábẹ́ ẹ̀ èrò pé náírà ló máa wò ó dàgbà ṣùgbọ́n ní ọjọ́ kọkànlélógún, oṣù Ọ̀pẹ, 2019; Ààrẹ Alassane oútara ti Ivory Coast pẹ̀lú u Emmanuel Macron àti púpọ̀ nínú àwọn orílẹ̀-èdè Uebìne, kéde pé àwọn kan máa yí orúkọ Cfa Franc padà ní kàkà kí àwọn rọ́pò rẹ̀ bí wọ́n ṣe rò tẹ́lẹ̀..
wikipedia
yo
Nàìjíríà di orílẹ̀-èdè àkọ́kọ́ ní Áfríkà láti san gbogbo gbèsè (ti ìdíye rẹ̀ jẹ́ $30 lẹ́gbẹẹgbẹ̀rún kejì) tó jẹ́ Paris Club padà ní April 2006.apá okoòwò Nàìjíríà jẹ́ orílẹ̀-èdè gbẹkun tó ń ta epo GURE Láyé, bẹ́ẹ̀ sì ni òun ní ikéẸwà tó ní ìpamọ́ epo G.“
wikipedia
yo
Epo Petrole ko ipa pataki ninu u okoowo Naijiria to ṣirò fun 40% gbogbo ipawo orile-ede (Jèhófà–ogofa) ati 80% iye owó ti ijoba n pa..
wikipedia
yo
DRItò jẹ́ ẹ̀yà kan lára àwọn olùgbé mẹ́ta àwọn ènìyàn orílẹ̀ èdè Rwanda and Burundi ní apá ìrin Afrika..
wikipedia
yo
Àwọn ògbẹyàn dó ń sọ èdè KW– èyí tí àwọn ènìyàn òtò àti ṣe ń sọ Afrika.
wikipedia
yo
Èdè Wolof jẹ́ Èdè tí a n sọ ní àti bèbè Senegal mílíọ́nù méjì-àbọ̀ niye àwọn tó ń sọ..
wikipedia
yo
Ìtàn ẹbí alámọyìdẹ́nu wọn sọ pé ọ̀kan lára àwọn tó kọ́kọ́ tẹ̀dó síbí yìí jẹ́ àwọn tó wá láti orífún Fulbẹ̃..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìtàn Wolof ni a le rí nínú àwọn orin oríkì èyí tí a ma ń gbọ́ láti ẹnu àwọn 'ots'ots' àwọn akéwì..
wikipedia
yo
Woyónì Agbegbe Congo (Zaire) ni a tin i awọn eyan wọ̀yọ̀..
wikipedia
yo
Ṣùkú ti jẹ́ ọ̀kan lára kéréje ẹ̀yà tó wà lábẹ́ yaká rí. Nípa ṣíṣe òde ni ọ̀nà tí àwọn ọkùnrin yàká ń gbà ṣápẹ́ wọn láti gbé ètò ọrọ̀ ajé..
wikipedia
yo
Eyi fihan pe kii ṣe òfìfo ni ó bá Ile-Ife, bi ko ṣe pe àwọn kan wa nibe pelu Aoridindin)".
wikipedia
yo
wọn ní ìlànà tó sọ bí a ṣe ń sọmọ lórúkọ àti irú orúkọ tí a lè sọ ọmọ torí pé ilẹ̀ là á wò, kí a tó sọmọ lórúkọ..
wikipedia
yo
Ìlànà ati ètò wà tí wọn ń tẹ̀lé láti sin ara wọn tó papòdà..
wikipedia
yo
Àárọ̀, Igbe ọdún dìde, Ìsìngba tàbí oko Olówó, gbàmí-ó-rámì àti eéṣú tàbí eṣúṣú jẹ ọ̀nà iran-ara-ẹni-lọ́wọ́..
wikipedia
yo
Àwọn àṣà tó jẹ mọ́ ẹ̀tọ́ ìbágbépọ̀ láwùjọ Yorùbá ni Èkó-ilẹ̀, ètò-ìdílé, ẹlẹ́gbẹ́jẹgbẹ́ tàbí ìròṣirò..
wikipedia
yo
A lè ríwọ́n ní Nàìjíríà, Gánà, Orílẹ̀-Olómìnira Bene, Togo, Saró àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Tí a bá ń fojú iṣẹ́ ọnà wò ó ọ̀rọ̀ kan tó jẹ́ x ní ìpín onítumọ̀ àdámọ̀ (ìsọ̀rí ọ̀rọ̀) Y ní Abgé tó ṣáájú ọ̀rọ̀mìíràn z, wíwà níbẹ̀ z jẹ́ fipá..
wikipedia
yo
Àkọsílẹ̀ àfòyemọ̀ ti òkè yìí ni a ń pè ní Apínbpín sí ìsọ̀rí tó múná dóko ni a jíròrò lé lórí Yusuf (1997 (1997).Tí a bá padà sí àwọn àpẹẹrẹ (1,2 ti òkè, ẹni tí ń sọ̀rọ̀ lórí bí a ṣe lè mọ àwọn tí ó dá dúró yìí tó jẹ́ ọ̀rọ̀ orúkọ tí ó lè wà ní ipò tó ṣe kókó; Olúwa àti àbọ̀..
wikipedia
yo
Wọ́n fẹjọ́ èṣù sọ nínú Bíbélì pé ó ń gba Efa níyànjú láti má bẹ̀rù nípa jíjẹ èso èèwọ̀, tó wí pé, “Ẹ̀yin kò ní kú kan”..
wikipedia
yo
Àwọn baba ńlá wa máa ń lo oríṣìíríṣìí irin iṣẹ́ láti wá ohun jíjẹ lára wọn ní àdá, ọ̀kọ̀, àgbọn, akọ́rọ́ ati bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Irinṣẹ́ àwọn ọ̀mọ̀lé, ahunṣọ, àwọn alágbẹ̀dẹ ni yóò rọyín jáde..
wikipedia
yo
Ero mohunmaworan, asọ̀rọ̀, Ero ti n fẹ atẹ́gùn (fan), ero to n fẹ tutu fe gbígbóná (Air condition) apẹẹrẹ mìíràn ni ero ibanisoro, alagbeeka, ero komputa, ero alukaleluko (Internet)..
wikipedia
yo
Àwọn àléébù tí wọ́n náà wà, ṣùgbọ́n ìṣe àti ìwúlò wọn kò kéré rárá...
wikipedia
yo
Wọ́n ma ń fi igbá àti ṣe àmì Ọbàtálá àti Odùduwà nígbà tí Oriori igbá ń rọ́pò Ọbàtálá ti ìyá igbá sì ń dúró fún Odùduwà gẹ́gẹ́ bíese Ọlọ́fin Ọ̀yéte tí ó túmọ̀ sí ẹni tí gba igba iye lọ́dọ̀ Elédùmarè.Ẹ tún le wo àtòjọ àwọn ọba alayé Ilé-Ifẹ̀ àwọn Akon ìgbà ìwáṣẹ̀ tilẹ̀ àtikaàwọn ìtọ́ka ṣíwọ́ eleyĩ náàliàṣeyọrí Odùduwà Afèsì ìkà Ojúojú, J..
wikipedia
yo
Ọgbọ́n ìmọ̀ àti òye tí Olódùmarè fi fún Ifá ló fún Ifá ni ipò ńlá láàárín àwọn ìbò ilẹ̀ Yorùbá …A kéré-finú-ṣọgbọ́n"ní oríkì ifá..
wikipedia
yo
Ẹsẹ̀ amọ̀mọ ni èyí kò yẹ kí ifá máa fẹ́ ìyàwó lórí ara wọn..
wikipedia
yo
Bí ó ti wà ní Líkì ni ó wà ní gbanjà obìnrin lékè obìnrin lọ́dálẹ̀ kénìyàn ṣe pẹ̀lẹ́ kí ó má finú han f'oo·ll Adéoyè pg 243 ẹ̀sẹ̀ ifá kan nínú Ọ̀bàrà méjì)ifá tẹ̀ síwájú nípa pípè àwọn obìnrin ní dokòkòkò àti alágbèrè..
wikipedia
yo
Fi obìnrin ẹ yalé yalé aláìnísuru a ri eleyi ninu sixteen great Poems of Ifá not long again..
wikipedia
yo
Ọ̀rúnmìlà ti gbàgbé pé bi ọjọ́ oore bá pé aṣiwèrè á gbàgbé àti pé ìwọ̀n ni oore..
wikipedia
yo
Nítorí ó dúró gẹ́gẹ́ bí agbára ìtúsílẹ̀ àti agbára hayéṣe..
wikipedia
yo
Nígbà tí Ọ̀rúnmìlà fẹ́ ṣe ìpàdé a kọ́kọ́ gbìyànjú láti bi ìfà léèrè lórí bí ìpàdé yóò ṣe rí ni wọ́n ban ì kó lọ bó Ṣàngó ojú eérú torí kẹ̀ nǹkan bá le sẹ́nu ìre àti pé kí àṣírí tó farasin lè bá hàn sáyé..
wikipedia
yo
Ṣugbọn orílẹ̀ èdè bíi Gíríìsì (Greece) tí ìṣirò ti bẹ̀rẹ̀, ilẹ̀ Lárúbáwá (Arabia), ilẹ̀ islétí ati bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, wà ninu àwọn irú eniyan tí ó tayọ ninu ètò ìkọ́ni..
wikipedia
yo
Ní ilé ẹ̀kọ́ girama ẹ̀wẹ̀, àwọn ohun tí àwọn akẹ́kọ óò máa há sórí - àkọ́sórí àwọn akẹ́kọ yóò dín kù, yàtọ̀ sí tíì Ilé Ẹ̀kọ́ ‘Oòsìmẹwa
wikipedia
yo
Ní ilé ẹ̀kọ́ gíga akẹ́kọ ní ànfààní láti ṣe ohun Towùú nígbà tí ó bá fẹ́ ti kòsí olùkọ́ tí yóó náà lọ́wọ́ wọ̀..
wikipedia
yo
Bí wọ́n ṣe ń ṣe èyí ni ọ̀rọ̀ elẹ́yàmẹyà bẹ̀rẹ̀ sí ṣẹlẹ̀, àti àwọn ìṣòro tí ó rọ̀ mọ́ elẹ́yàmẹyà..
wikipedia
yo
Owó ló gbé àwọn òyìnbó dé ilẹ̀ aláwọ̀ dúdú, wọ́n wá ri pé yio rọrùn fún àwọn lati ri nǹkan àlùmọ́ọ́nì ti wọn n fẹ́ ti àwọn bá mu ilẹ̀ aláwọ̀ dúdú sìn..
wikipedia
yo
IKÚ ọmọ ọba yìí ló ṣokùnfà ogun àgbáyé nígbà tí orílẹ̀-èdè ènìyànríria-Hungary gbaná jẹ..
wikipedia
yo
Nígbà tí ilẹ̀ Austria-Hungary ríbi tí ọ̀rọ̀ yìí ń tọ̀, wọ́n tẹsẹ̀ dúró fún ìjíròrò pẹ̀lú ilẹ̀ Russia..
wikipedia
yo
ní ọjọ́ kejì sí èyí ni ilẹ̀ ní ilé France náà kéde ogun lé ilẹ̀ Germany náà lórí..
wikipedia
yo
Yorùbá tún bọ̀ wọ́n ní "Ẹni tí Ṣàngó bá tọ́jú rẹ̀ jà rí kò ní báwọn bú Olúkókókósọnù..
wikipedia
yo
ÈÉ ṢE NI wúnrẹ̀n ti éí maa n lo fún ìyísódì olùwà nínu gbólóhùn àkiyèsí alatẹnumọ́..
wikipedia
yo
Ọ̀nà tí éí ń gbà tọ́ka ìba-ìṣẹ̀lẹ̀ yìí yàtọ̀ gegbẹ́gbẹ́ sì ti ya..
wikipedia
yo
Àwọn múudú wọ̀nyí ni à ń dá pé ní ojúṣe lóhun, àníyàn àti kànńpá lédè Yorùbá..
wikipedia
yo
ṣaláìwù (2005) o gba yoo gẹgẹ bi atọ́ka asiko ọjọ-iwaju tabi ojuse..
wikipedia
yo
syra (ADV); nínú ọkọ ojú omi tàbí òfúrufú; the Captain Welcomes you aboard this plane..
wikipedia
yo
Ún (AD); ko si, ko wa; he was in from work last Tuesday Tuesday
wikipedia
yo
absolute (ADAD); pátápátá; Ámínádì has absolute Freedom to Surhi a Husband..
wikipedia
yo
(Ọ̀kan lára àwọn òṣèrébìnrin ìwòyí ni Liz Benson ń ṣe)..
wikipedia
yo
(A kọ́ ilé ìjọ́sìn yìí ní ẹgbẹ̀rún méjì ọdún ó dín díẹ̀ lẹ́yìn ikú Olúwa wa)..
wikipedia
yo
(Ẹ̀yindíye méje ló wà nínú apẹ̀rẹ̀, mo fi mẹ́ta kún un, ní bá yìí ó ti di mẹ́wàá..
wikipedia
yo
ADEADE Akande, tí ó padà di gomina ní ìpínlẹ̀ Osun ni ó jẹ́ igbékejì rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí gomina nínú ẹgbẹ́ iselu UPN nígbà náà.Ni inú ìdìbò ọdún 1983, ti Bola tún dí láti padà sísí gomina lábẹ́ abúrada UPN, ọ̀péwe Victor Omo Olúnlo lo feyin rẹ̀ balé nínú idije ibo sipo sí gomina naa..
wikipedia
yo
Èkejì sọ fún wa pé ti àkójọpọ̀ nọ́ḿbà gidi ti kí ṣe ọ̀fọ̀ (empty) bá ní ìparí l'òkè (Upper Bound), ó gbúdọ̀ ní ìparí l'òkè tókéréJùlọ..
wikipedia
yo
Àwọn méjèjì yí lápapọ̀ ni wọ́n ṣe'túmọ̀ nọ́mbà gidi pátápátá..
wikipedia
yo
(Èyí sísí nọ́ḿbà gidi tí wọ́n ọ̀gágun sí gbòǹgbò alágbáraméjì 2). Àwọn òpin wà fún àwọn ìtẹ́lẹ̀ntẹ̀lé Cauchy ní Ìṣirò Kalkúlòsì fi ṣe é ṣe, tí ó sì wúlò..
wikipedia
yo
Ọna kan ti a fi le ṢÈWÀdi boya itẹmọn kan ni opin ni ki a yẹ̀wò boya o jẹ itẹmọn Cauchy, nitoripe a ko le mọ opin yi tẹlẹ.Fun apẹrẹ etonọmba (series) fun igbega alábáalábáse (Exntintinti function) si nọmba gidi kan, nitoripe fun gbogbo x awon aropo le kere gan ti a ba jẹ ki n o tobi dáada..
wikipedia
yo
Àwọn ni Ọ̀jọ̀gbọ́n Bísí Ògúnṣínà, Arábìnrin Comfort Ogunmọla, Arábìnrin Aarinpe Adéjùmọ̀, Olóyè Olufemi Abibi, Arábìnrin Olayinka Aeso, Lel Agboọlá, ònkàle Ajayi, àwọn akẹ́kòọ́ ti mọ̀ kọ́ ni ẹ̀ka-èdè Ẹ̀ka-èdè Yorùbá láàárín ọdún 1991- àti àwọn aláṣe ilé-iṣẹ́ A- Monrin Paper—
wikipedia
yo
Nígbà tí ọba ìgbàmọ̀ - Jẹ̀ṣà bá ń bộ wálẹ̀ lẹ́hìn ọ̀pọ̀ èbí tí ó ti lọ ní Ileṣa fún ọdún ogun, Ọtáforíjọfa ni àwọn ènìyàn rẹ̀ ti gbọ́dọ̀ pàdé rẹ̀..
wikipedia
yo
Nítorí pé agbára ti kún agbára ọba ọ̀tá Ọba Ijẹ̀bú - Jẹ̀ṣà yí, ó wá dàbí ọwọ́ fẹ́ tẹ Ọba Ijẹ̀bú -Jẹ̀ṣà àti àwọn ènìyàn rẹ̀ ni òun náà bá sá tọ ọba ìlú Ilaye lọ fún ìrànlọ́wọ́..
wikipedia
yo
Ni ọdun 1952, oun ati Chris OgunBanjo,Oloye Bode Thomas ati Michael Odesanya kóra jo po di okan.Ìtọ́kasíàwọn oloselu ara Naijiria..
wikipedia
yo
Nọmba gidi a ni a n pe ni apa gidi nọmba tosoro, bẹ ṣini nọmba gidi b jẹ apa Àǹfààníìdámẹ́wàá
wikipedia
yo
Nínú ìmọ̀ iṣẹ́-ẹ̀rọ ìrúyà (báka Engineering), níbi tí í ti dúró fún ìwọ ina (eleriatric Current) Àmì tí a ń lò fún ẹyọ GG í ní J, Ari bá pé nígbà míràn nọ́wà tó ṣe kò lé bá bá, A +Al Seòkutats nọ́guẹ̀kọ́ Mathiki Mathi
wikipedia
yo
Orúkọ àwọn ìyàwó rẹ̀ láti orí ìyàwó àkọ́kọ́ ní Muibatu Oriyinrin, Fọláṣadé Akita, Mopelá Ìṣọ̀lá, Deborah akérégbè àti Iyabo Ailorin..
wikipedia
yo
Nínú orin tí ó kọ fún Gbenga Adeboye, ó jẹ́ kí a mọ̀ pé òun sí ni ìyá láyé nítorí pé ó ní òun tí bá Gbenga Adeboye sọ̀rọ̀ pé yóò bá òun sin ìyá òun lọ́jọ́ tí ó bá relé ogbó.Àwọn ìtọ́ka síÌjápọ̀ lódeàwọn àwo-orin Dr..
wikipedia
yo
Àtòjọ àwọn àagberòrò tí wọ́n jẹ́ ọmọ Unọn looya àkọ́kọ́ ní ilẹ̀ Nàíjíríà tí wọ́n jẹ́ ọmọ Yorùbá..
wikipedia
yo
Ọmọ Yorùbá ni Corsoréètì kìíní ní ilẹ̀ Nàìjíríà tí ó jẹ́ ọmọ Nàìjíríà ní sir Olumúwáwá Kabruru..
wikipedia
yo
Lọ́yà obìnbin akoko ti o je omo Naijiria ti yoo di adajo ile ejo agba (High Court Judge) ni ile Naijiria ni Mrs Mogbo Ọmọ-ẹbọ ti o je omo Akingbẹ̀hìn..
wikipedia
yo
OMẸ́Mrs Folake s 'Attorney-General' ti ti yoo jẹ̀kọ Naijiria akomo'o Naijiriaile ni Dr di 'President ofko AFIErika ti yoo ko ileọmọlà Elias oun ni Otes o Yoruba nie International Court of Jucesbẹ̀rẹ̀
wikipedia
yo
absolute (AD€); pátápátá; Ámínádì has absolute Freedom to Jóòbù a Husband..
wikipedia
yo
Àwọn alágbẹ̀dẹ ló sì máa ńjẹ "Eji" èyí ló fà á kìkì wọn ní "EjiWanda ará ilagbẹ̀dẹ̀” 🙂
wikipedia
yo
A gbọ́ pé ibi tí Odùduwà àti àwọn ẹmẹ̀wà rẹ̀ rọ̀ sí ni wọ́n ń pè ní Òkè Oọ̀rám lónìí..
wikipedia
yo
In fact Ilé-Ifẹ̀ is Fáled as the spot where God created man White and Black Black From Whence They disìwọ̀n All over the Earth .(Gbogbo ẹ̀yà Yorùbá ló tọsẹ̀ orírun wọn sí Odùduwà, a tilẹ̀ gbọ́ ọ nínú ìtàn pé Ilé-Ifẹ̀ ni Ọlọ́run ti ṣẹ̀dá ènìyàn, yálà funfun tàbí dúdú tí wọ́n sì ti ibẹ̀ fọ́n káàkiri ilẹ̀ ayé)..
wikipedia
yo
Àwọn mìíràn gbà pé àwọn méje wọ̀nyí kì í ṣe ọmọ-ọmọ Odùduwà, pe ọmọ Odùduwà gan-an ni wọn àti pé kì í ṣe ìyàwó kan ṣoṣo ni Odùduwà ní..
wikipedia
yo
Bóyá ìdí nìyí tí wọ́n fi máa ń kí àwọn Òwu ní Asunkún Gbadédé Ọmọ Akín Omini Gbodo Ọmọ Igboáàkórọ, àrìnká jí kùtù Kúú ìgboro bójú Ẹ̀ko Odùduwà tó kù lẹ́yìn olówu ní Aláké ti Ketu, Ọba Ìbìní, Ọ̀ràngún Ilẹ̀ Ìlà, Onisábẹ́ ti Ilẹ̀ Sawó, Olùpópó tí Í Ṣe Ṣe Àpópó àti Ọjùadé
wikipedia
yo
Ìjìyà kò sí nílẹ̀, àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ sì pín gbogbo dúkìá baba wọn mọ́ owó, ilẹ̀ nìkan ni wọ́n fún un..
wikipedia
yo
Àwọn Yorùbá tó si wà ni orílẹ̀ èdè Benin pin si méjì ‘ìdá' àti ‘Manioṣù
wikipedia
yo
Oun pelu awon Ìyòókù re bíi ògbójú ọde ninu Igbo Irúnmọ́lẹ̀, Ìrèké Onibù, Irindodo ninu Igbo Elégbèje ati Igbo Olódùmarè, ti D.O Fágúnwà ko jẹ okan gboogi lara iwe ti awon omo ilẹ̀ilẹ̀ giga Yunifásítì tàbí ilẹ̀ilẹ̀ àwọn olùkọ́ni fún iṣẹ́ akadá lọ́pọ̀ ìgbà..
wikipedia
yo
Fágúnwà (2005) Àdììtú Olodù Ibadan; Evans Brothers (Nigeria Publishers) Limited, ISBN978-126-126-7..7
wikipedia
yo
orísun fún àtòjọ àkókò a list àwòyín, délẹ̀, 1992 pages 30–35.35.
wikipedia
yo
This list was already in use before 2015.This ìfọbàjẹ́ kì í ṣe iṣẹ́ tó rọgbọ rárá, ó sì ní àwọn tíwọ́n fi sípò láti máa fọba jẹ..
wikipedia
yo
OyoTunji Àpéjọpọ̀ Àwọn kan ní yí tí wọ́n ń gbe èdè àti Àṣà Yorùbá Lárugẹ..
wikipedia
yo
Wọ́n pe ibi tí wọ́n wà ní The Kingdom of OyoTunji, Box 51, Yoruba Village, South Carolina 29941..
wikipedia
yo
Ilé-Ifẹ̀ ni Ọba yìí ti wá gba adé ní ọjọ́ karun-un oṣù kẹfa, ọdún 1981 ni ààfin Ọba Okunade Sijúwadé, Olùbushe keji..
wikipedia
yo
Eyi si ni igba akoko ti eni ti kii se ọmọ ile Naijiria yoo gba ade ni Ile-Ife..
wikipedia
yo
OyeWale, 'àgbéyẹ̀wò ewi Ayaba laarin àwọn Oyo-Osun'., apileko fún oyè Eèmẹ́ẹ̀l, Dall, OAU, Ife, Nigeria..
wikipedia
yo
Láti bu ọla fún pẹ̀lú ipá rẹ̀ láti lè jẹ́ kí ìjọba Ọ̀yọ́ tí ó ti ń dẹnu kọlẹ̀ ó tún gbiná ya nínú àwọn ogun tí ó mú Ọ̀yọ́ borí ilẹ̀ Ẹ̀gbá, Ìjẹ̀bú-rẹ́mọ yí ni ó mú kí wọ́n fi jẹ́ ''Ààrẹ àgọ́ ilẹ̀ Ìbàdàn’’..
wikipedia
yo
Oun naa si fi ara rẹ jẹ oye ''O-kakanfo’’, ti o so o di Ologun apàṣẹ wàá kẹta fun ile Ibadan.Ìwé Àmúlò Akínwùmí Atanda (200) Baṣọ̀run Oluyọlé Ibadan; Rasmed Publications, ISBN80-24-24-24-0..0..
wikipedia
yo
Àkòrí ìwé àpilẹ̀kọ àkọgboyè náà ni “Àsìkò àti Ìbà-Ìṣẹ̀lẹ̀ Nínú Ẹ̀ka-Èdè Yorùbá mófoli” (Tense and Aspect in the Olumófoli Dict of Yoruba)..
wikipedia
yo
...Àwọn nǹkan pàtàkì tí ìfà máa n dá lé lórí òrò nípa orí,ẹsẹ àti aya ìwà ìtàn àwọn òrìṣà àwọn ajogún àti àwọn ẹlẹyẹ ẹbọ ire àti àkíyèsí nípa ẹ̀dáìwé fún kíkà j..
wikipedia
yo
A Lijàdú (1895) Ifa Mimọ Alabate United Star Printers Ltd.
wikipedia
yo
Ọdúnjọ (1969), ẹ̀kọ́ ìjìnlẹ̀ Yorùbá _ fún àwọn ilé ẹ̀kọ́ gíga, apá kejì, Long of Nigeria, ojú-ìwé 88-94...
wikipedia
yo
Pabe lo, pebẹ BO Aroko ni lati Eko titi de 'bàdàn, ko si moto bẹẹ ni ko si bata lẹsẹ boorun ti n pawo ori, ...Akínwùmí feyin tiAkínwùmí fọmọ tíórere ilé ayé rèé, ko sóhun to tarẹ ti o ni i lopin jọjọ boorun ti lagbara to, Tina ọmọ o n pa Wi-tọmọ bọ-tọmọ pe bo ya oju ojo a ro wòó, oorun a si wọ̀ọ̀kùn, ààjìn dùndún..
wikipedia
yo
Bó ti wù kómọdé gbádùn eréwọlé tó.Bó bá paná, eré a sì ríransinsin,orí mi àpé mi mi àpé orí mi àpé, àyà mi àkọ́bí-bọ̀ nígbà tórí ń gbéni kín ẹlẹ́rò ń wò? Orí lèjà fi í làbù jà, orí lọKá fi í ṣe rere lálẹ́ odò orí la fi í meran láwọ̀ tá a kì í fi í meyìí tó leegun orí lobìnrin fi í yan ó nwé àyè ayé, orí lobìnrin fi í jókòó ọkọ rẹ̀ kò tóó dọjá gayìnùn..
wikipedia
yo
Orúkọ àwọn wọ̀nyí jẹ́ sísọ mọ́ “Afa” tí àwọn finikì, tó túmọ̀sí “Eruku", ṣùgbọ́n èrò 1981 kan ti sọ pé ó wá láti ọ̀rọ̀ èdè berber Ifrí tàbí Ifran totúmọ̀sí “CAv", in Reference tó cave jasperive..
wikipedia
yo
Ìdí rèé tí oore fi kúrò ní agbègbè ìlú rẹ̀, tó fi kọrí sí agbègbè Ákílápá níbi tí igbó ńlá wà..
wikipedia
yo