cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ìtẹ́ náà ni a túnrí nígbà ìdarí Marinid Sultan Abd Al-haQq Kejì (14-14–65) ní 1437, to si di ibi pataki ati mimo ni ilẹ Fez.itọkasi..
wikipedia
yo
Oko ẹrú ní etíkun ti Barbary (owó oko ẹrú ní etíkun Barbary) jẹ́ iṣẹ́ làbirá ti kin ṣe ọ̀fẹ́ tó wáyé lãrín century ti mẹ́rìn dínlógún àti méjì dínlógún ní agbègbè Etíkun Barbary ní apá àríwá ti ilẹ̀ Áfríkà.Ìjà Ògùn ti Barbarygẹ́gẹ́bí ìwádí Robert Davis, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ará ilẹ̀ Europe ní àwọn olè abẹ́ omi ti Barbary kó tí wọ́n sì tà wọ́n lẹ́rú ní àríwá ilẹ̀ Africa àti àfin ti Ottoman lãrín century ti mẹ́rìn dínlógún àti ọ̀kan dínlógún.Láti ìsàlẹ̀ ti etíkun ti Barbary, àríwá ilẹ̀ Áfríkà, àwọn olè abẹ́ omi já ọkọ̀ ojú omi gba èyí tó ṣe ìrìn àjò lọ sí Mediterranean, àríwá àti ìwọ̀ oòrùn etíkun ti ilẹ̀ Africa tí wọ́n sì kó àwọm èrò bẹ̀ lẹ́rú.From at Least 1500, The àwọn olè abẹ́ omi yí tún kógun ja àwọn ìlú etídò tó wà ní ilé Italy, Spain, France, England, Netherlands àti Iceland tí wọ́n sì kó obìnrin, ọkùnrin àti ọmọdé lẹ́rú..
wikipedia
yo
Lrin ọdún 1609 àti 1616, England pọfọ̀ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọkọ̀ ojú omi sí ole abẹ́ omi ti Barbary lọ́wọ́.Ọ̀rọ̀ nípa oko Ẹrúnínu Àfiwé Ọ̀rọ̀ nípa Ẹrú ti Ariwa ilẹ̀ America àti Ọ̀rọ̀ nípa Ẹrú ilẹ̀ Caribbean ní èdè Gẹ̀ẹ́sì ní àwọn ẹru aláwọ̀ funfun ti ilẹ̀ America àti British kọ́..
wikipedia
yo
Ọ̀rọ̀ yìí ló yàtọ̀ sí ìsọ̀kam ti àwọn oníṣòwò ẹrú ti ẹlẹ́sìn Mùsùlùmí, ṣùgbọ́n ọ̀rọ̀ àwọn ẹrú ti Africa-America máa npe àwọn oníṣòwò ẹrú ni ẹlẹ́sìn Chrisdélẹ̀.Ọ̀rọ̀ tó dá lórí òmìnira tó jẹ́ òun ìwúrí láti ilẹ̀ America.Nígbà tó jẹ́ pé àwọn ọ̀rọ̀ yí wọnú ara wọn, àwọn onímímọ́ gbàgbọ́ pé púpọ̀ nínú àwọn ọ̀rọ̀ yìí ju ti àwọn tí wọ́n kó lẹ́rú lọ..
wikipedia
yo
Awon obinrin ti won ko lẹ́rú ni won lo ni Gothic fiction to tumọ si imọlẹ imonira ti awon ara ti oun wo gbagbo.itọkasi..
wikipedia
yo
.Etíkun oko ẹrú yí jẹ́ orúkọ àdáyébá tí a ti lọ tẹ́lẹ̀rí fún apá etíkun ìwọ̀ oòrùn ní agbègbè Bight ti Biafra àti Bight ti Benin tó wà ní ãrín odò Volta àti Lagoon ti Èkó.Orúkọ yí ni a yọ látàrí ìtàn agbègbè náà gẹ́gẹ́bí ọ̀nà kan gbógì tí àwọn ẹ̀yà Áfríkà ma ńkọ lẹ́rú ní ọwọ́ oko ẹrú ti Atlantic láti Century mẹ́rìn dínlógún lọsi Century ti ọ̀kan Fálógun.Ìta àwọn ènìyàníto..
wikipedia
yo
Etíkun ti Barbary (a tún mọ̀ sí Barbary, Berbery tàbí Etíkun ti Berber) jẹ́ orúkọ tà fún agbègbè etíkun ti àríwá ilẹ̀ Áfríkà tàbí Mahhreb pápá jùlọ ibùdó Ottoman pẹ̀lú rẹ̀ ní adelé tó wà ní Algiers, Tripoli, Beylik ti tunis àti Sultanata ti Morroco lati century ti mẹ́rìn dinlogun dé ọkám dinlogun..
wikipedia
yo
Orúkọ yìí ni a fàyọ láti Exonym tí àwọn Berberitan.Ìtàn Etíkun ti Barbartọ́kasí..
wikipedia
yo
Ìjà ìkólẹ́rú ti ṣudúróy jẹ́ ìjà tí àwọn àfìgbà ọkọ̀ ojú omi láì àríwáìwọ̀ oòrùn ilẹ̀ Áfríkà tó ṣẹlẹ̀ ní ṣúdúróy ní erékùṣù fàroe ní Summer ti ọdún 1629..
wikipedia
yo
Èyí ló jásí ìjínigbé àwọn ènìyàn ọgbọ́n tí wọn obìnrin àti ọmọdé tí wọ́n kòkú ní etíkun ti Barbary ti àríwá ilẹ̀ Áfríkà.Gbogunítoji..
wikipedia
yo
Turkish Abductions (tí ó túmọ̀ sí "àwọn ìjínigbé ní orílẹ̀ èdè Turkey–agbègbè Mediterranean nígbà náà) jẹ́ oríṣi ìkónilẹ́rú tí àwọn jàndùkú ojú omi láti àríwá ìwọ̀ oòrùn Áfíríkà ṣe ní orílẹ̀ èdè Iceland ní igba Òru Ọdún Secrise.Àwọn jàndùkú ojú omi náà wá láti ìlú Algiers àti Sale..
wikipedia
yo
Wọ́n ya wo GrindaVik, East Fjörds, àti Vveyjar..
wikipedia
yo
Ènìyàn bí àádọ́ta ni wọ́n pa àwọn ènìyàn irínwó ni wọ́n kọ̀ tí wọ́n sì tà ní oko ẹrú..
wikipedia
yo
Wọ́n padà san owó fún wọn ní ọ̀pọ̀ ọdún lẹ́yìn ìsẹ̀lẹ̀ náà, láti dá ènìyàn tí ó tó ààdọ́ta padà.àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Moulay Ismail Ibn Shaf (), ti a bi ni okoo ni ṣíjilMassa ti o si fi aye sile ni ojo kejilelogun osu keta osu 1727 ni Meknes, je Sultan Morocco lati odun 1672 si 1727, gege bi adari keji 'Alaru dynasty..
wikipedia
yo
Oun ni ọmọkunrin keje Moulay Shaf o si fi igba kan jẹ Gomina agbegbe Fez ati ariwa Morocco lati ọdun 1667 titi di igba iku arakunrin rẹ, Sultan Moulay Rasd ni ọdun 1672..
wikipedia
yo
Wọ́n kéde rẹ̀ gẹ́gẹ́ Sultan ní fefe, ṣùgbọ́n oun àti Moulay Ahmed ben MehReza, ẹni keji tí ó pe ara rẹ̀ ní Sultan ja fun opo odun, Moulay Rasd pada fi aye sile ni odun Tẹ́gun..
wikipedia
yo
Moulay Ismail wa lori oye fun ọdun marunladọta, eyi si mu ki o jẹ Sultan ti o pe lori oye ju ni Morocco..
wikipedia
yo
Nigba ayé rẹ̀, Moulay ni iyawo ti o to ẹẹdẹgbẹta ati ọmọ ti o to ẹgbẹrin.Àwọn itọkasi..
wikipedia
yo
Oko Ẹrú Barbary jẹ́ àwọn Ọjà Ẹrú tí ó wà ní àwọn ìpínlẹ̀ Barbary..
wikipedia
yo
Awon jàndùkú odo ti o je omo Barbary ya wo awon oko oju omi, ilu egbe odo lati Italy de Netherland, Ireland ati guusu apa iwo Oorun Britain, titi de ariwa Iceland ati ila-oorun MediTerra.Apa ila-oorun Mediterranean Ottoman ni isele yi WÒSÌ julo..
wikipedia
yo
Títí di àwọn ọdún 1700s, ìwà jàǹdùkú jẹ́ nkan tí ó sì ń da Aegean láàmú.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Onya - October 1872) jẹ́ ẹrù Nupe tí ó gba òmìnira tí ó sì padà di oníṣòwò àti olóṣèlú ńlá ní orílẹ̀ èdè Sierra Leone..
wikipedia
yo
Wọ́n tu sílẹ̀ ninu oko ẹrú tí ó ń lọ sí orílẹ̀ èdè Brazil, ó kọ́ iṣẹ́ lábẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Faransé kan, ẹni tí ó kọ́ bí a ṣe ń kọ́ ati kàwé..
wikipedia
yo
Eedidiidi pada de ipo Mayor Ilu Freetown o si pada di ara awon omo egbe igbimo Gomina igba naa.ijigbe re won ji Baazidio, omo eya Nupe gbe fun eru ni agbegbe ti a wa mo si ipinle Niger loni, won si gbe wa si ibi ti eya Yoruba wọpọ si..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1827, wọ́n tà fún àwọn fún àwọn ìjísí, àwọn ìjísí sí fi sínú ọkọ̀ omi tí ó ń lọ sí orílẹ̀ èdè Brazil..
wikipedia
yo
Royal Navy dá oko náà dúró wọ́n sì tú ÉèITidi àti àwọn àwọn tí ó lé ní nírí míràn kalẹ̀, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹrù tí ó yẹ órin bá́nnà, Sierra Leone ní Oṣù Kẹwàá ọdún 1827.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
John Jea (1773 – Lẹ́yìn 1817) jẹ onkọwe, oníwàásù ati awakọ̀ oju omi ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹrika mọ́ Afirika..
wikipedia
yo
O gbajumọ fun iwe rẹ ti o kọ ni ọdun 1811 The Life, History, And Unparalleled Toríls of John Jea, The African Preacher..
wikipedia
yo
Je di ẹru lati igba ti o si jẹ ewe, leyin igba ti o si gbòmìnira ni 1790s, o bẹrẹ si n ririn ajo ati waasu kaakiri.ipilẹ !’ ni a mo nipa ipilẹ John jẹa yato si oun ti o ko ninu iwe rẹ, The Life, History, and Unparallele Toríls of John Jea, The African Preacher (1811).A sọ pe won bi ohun ni Africa ni ọdun 1773 lẹgbẹẹ Calabar ni Bight of Biafra, ati pe awon akónilẹ́rù ji oun, awon obi oun, Hambleton Roberta ati Margareta ati Margareta, ati awon ebi oun gbe, won si ta awon fun ẹru si New York City, iṣẹlẹ si ṣe nigba ti o si je omo odun meji ati abo..
wikipedia
yo
Ìdílé Dutch kan, Oliver and angẹlika Triokeen, rà jẹá..
wikipedia
yo
Àwọn olówó rẹ̀ jẹ́ ọmọ ìjọ Conservative Dutch búbó, tí ó lòdì sí yíyí ẹ̀rù sí ẹ̀sìn Kritẹni..
wikipedia
yo
Awon Olowo re ma n lo si ile ijosin lati ba wi sugbon jea di kristeni, a si se Ìrìbọmi fun ni 1780s.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Dial S'nagbálẹ̀ (tí a bí ní ọdún 1880) jẹ́ atúmọ̀ èdè (tí ó wá láti ibi tí Nàìjíríà wà lókàn) tí ó tètè Arìnrìn-àjò Faransé kan tí orúkọ rẹ̀ jẹ́ Lieutenant Midọ́gba.Ìtàn rẹ̀ a bí ọpẹ́ty S'nagbálẹ̀ sínú Ìdílé Olóyè Konanki, nínú ìlú Íbe, lẹ́gbẹ̀ẹ́ lókọja níbi tí Odò Benue àti Niger ti pàdé..
wikipedia
yo
O gbo ede Faranse, Gẹẹsi, ati awon ede Niger miran..
wikipedia
yo
S'nagbálẹ̀ wa ni aṣsaba, nígbà tí o pàdé miZon tí ìyá rẹ̀ sì sọ pé kí o tẹ̀lé miZon ninu ìrìn àjò rẹ̀ lọ sí lókọjá kí o ba lè rí baba rẹ, nítorí miZon ń lọ sí lókọjá nígbà náà, S’nagbálẹ̀ jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́wàá sí mọ́kànlá nígbà náà..
wikipedia
yo
Ni Lodeja, S'naBou sọ fun baba ati iya baba rẹ pe oun fe tele miZon ninu irin-ajo rẹ lo si Moi, olu-ilu of Adamawa.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Chief Oshodi Lanji tàpá ( - Ibra) jẹ balogun ọba Kosoko ati ara awon oloye ti o lagbara ju lọ ni ààfin ọba Eko.ipilẹ rẹ opo gbàgbọ́ pe Oshodi tápá wa lati ẹya sin Nupe ni bida ti o wa labẹ ọba Obori..
wikipedia
yo
Idilé Oshodi sọ wípé nígbà tí olùtàpá jẹ́ ọmọde, àwọn ìdá já pinu láti gbé sínú ọkọ̀ omi Portugal tí ó ń lo Amẹ́ríkà ṣùgbọ́n ó sà ó sì lọ sí àfin àfin Òpapọ̀ fún Abo. rẹ̀ nítorí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀bùn tí ó ní, Oshodi tápá di aduadura fún Ọba Ògunsókè..
wikipedia
yo
Ọba Oṣìnlókun ran ohun ati ẹru miran (Dada Antonio) lọ si Brazil lati kọ́ èdè Portuguese, ati lati ni imọ ti o ṣe pataki lati gba owó ori lọwọ awọn oni ọwọ ẹrù Portugal..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ìgbà tí ó ṣiṣẹ́ fún òṣìlókun, Oshodi tápá di olùmọ̀ràn àti balógún ọba Kosoko.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
1826 – ti o si fi aye sile ni odun Ijora) je omo orile ede Sudan kan ti awon olókòwò eru Arab jígbé nigba ti o je omo odun mejo, ti won si mu wa si Scotland ni odun 1836, nibi ti won ti to dagba gege bi okunrin llómìnira..
wikipedia
yo
SeLim kọ ìwé nípa ayé rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ẹrú, ó sì sọ nípa òde tó Britain ní ọdún 1846..
wikipedia
yo
O ma opo ni Great Britain nipa Afirika, o si tele William BalFour Baìkìe ni 1857 lati lo Niger River..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn náà, ó tẹ̀lé John Haley Glover àti Richard Francis Burton nínú ìrìn àjò wọn káàkiri Áfíríkà..
wikipedia
yo
Ní àwọn ọdún 1860s, SeLim lọ sí Liberia, àwọn jàndùkú Grebó pa ní ọdún 1875.Ìgbà èwe rẹa bí SeLim àga, gẹ́gẹ́ bí ó ṣe sọ nípa ara rẹ̀, sínú pẹ̀tẹ́lẹ̀ taqaliali..
wikipedia
yo
Àwọn ènìyàn tàQali ń ṣiṣẹ́ àgbẹ̀ àti olùṣọ́ àgùntàn, ẹ̀sìn wọn ní Islam àti sísìn oorun..
wikipedia
yo
Àwọn akónilẹ́rù ji SeLim gbẹ nígbà tí ó ń da nǹkan ọ̀sìn baba rẹ̀..
wikipedia
yo
Ó sìn lábẹ́ olówó mẹ́wàá, ẹni kẹwàá ní Robert THurburn (Mr..
wikipedia
yo
Robert kò ṣeLim ní èdè SoLisi, won si mu lo cataracts of the nile.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Simon àbárin Deng jẹ́ ajàfẹ́tọ́ ènìyàn ọmọ orílẹ̀ èdè Sudan ti United States..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọmọ bíbí ìjọba Shillù ní gúúsù Sudan, Deng lo ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún gẹ́gẹ́ bí ẹrú ní gúúsù Sudan.ÌtànWọ́n kó Simon lẹ́rú nígbà tí ó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́sàn nígbà tí aládùúgbò rẹ̀ kan sọ pé kó tẹ̀lé òun lọ ìrìn-àjò kan..
wikipedia
yo
Deng tẹ́lẹ̀, ó sì fi Deng gẹ́gẹ́ bí ẹ̀bùn fún ìdílé rẹ̀..
wikipedia
yo
Nígbà tí mo jẹ́ ọmọ ọdún mẹsan-an, àwọn ọmọ ogun Arab ya bọ abúlé mi..
wikipedia
yo
tí mo ṣe ń ṣawó igbó ni mo rí tí wọ́n yin àwọn ọ̀rẹ́ mi kan, wọ́n sì dáná sun àwọn àgbàlagbà tí kò lè sáré ninu ilé wọn..
wikipedia
yo
Wọ́n jí mi gbé wọ́n sì fi mí fún ìdílé Arab kan gẹ́gẹ́ bí “Ẹ̀bùn.”Nígbà tí Deng jẹ́ ẹrú, ojú rẹ̀ rí lọpọlọpọ..
wikipedia
yo
Ó ní òún rántí bí wọ́n ṣe na òun nítorí kò pariwo tó, bí àwọn ọmọdé tó kù ṣe náà..
wikipedia
yo
Wọ́n fi ipá mú láti sọ bẹ́ẹ̀ni sí òun gbogbo, pẹ̀lú ìyà..
wikipedia
yo
O ni pe "nnkan ẹyọkan ti mo le bẹrẹ fun nigba miiran ni àánú....
wikipedia
yo
Trans-Saharan Trade tàbi Iṣowo laarin Sahara nilo irin-ajo koja Sahara laarin Iwo-oorun, Central, Ila-Ọ̀run ati Àríwá Afirika..
wikipedia
yo
Lakoko ti o ti n wa lati awọn akoko ti wọn pe ni Prehistoric Times, awọn akoko iṣaajuu, eyi ti o jẹ igba kan ti iṣowo gbooro wa ni oke téńté lati orundun kejo titi di ibẹrẹ orundun ketadinlogun.Sahara yii ti fi igba kan ri bii Sahara alawọ ewe ri, agbegbe ti o yatọ pupo si Sahara ode oni..
wikipedia
yo
Ni igba kan ri, ni ẹgbẹ̀rún ọdún méje sẹ́yìn kí a tó bí Jesu ni iṣẹ́ daran-daran àwọn ohun ọ̀sìn bí ẹran ewúrẹ́, àgùntàn, ti wà ní àwọn orílẹ̀ èdè bí òfuurufúya àti Algeria, pẹ̀lú iṣẹ́ fífi amọ̀ mọ nǹkan..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ẹgbẹ̀rún ọdún mẹ́rin sí mẹ́ta àbọ̀ ni iṣẹ́ dídá ẹran màálù ní Central Sàhárà ni Aahagar bẹ̀rẹ̀.Àwọn àwòrán àpáta ìyàlẹ́nu (ní 3500 sì 2500 BC) ní àwọn ààyè tí ó gbé lọ́wọ́lọ́wọ́, ṣe àfihàn àwọn òdòdó àti àwọn ẹranko tí kò sí ní agbègbè aginjù òde òní...
wikipedia
yo
Charles III (Charles Philip Arthur George; tí a bí 14 November 1948) jẹ́ ọba ti Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan àti 14 mìíràn Commonwealth ìjọba...
wikipedia
yo
William, Alade ti Wales, (William Arthur Philip Louis; tí a bí 21 June 1982) ní ajogún gbangba sí ìtẹ́ Britani..
wikipedia
yo
Oun ni ọmọ àgbà tí Charles III àti Diana, Ọmọ-bìnrin Ọba ti Wales...
wikipedia
yo
1928 - 16 December 2012) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ti orílẹ̀-ède Scotland..
wikipedia
yo
Patterson jẹ́ agbábọ́ọ̀lù tó máa ń gbá bọ́ọ̀lù tó pọ̀ jù lọ sáwọn fún ẹgbẹ́ Dumfries Queen of the South, pẹ̀lú góòlù 251.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Michael Nozik jẹ́ ara ìlú America tó máa ń gbé fíìmú jáde..
wikipedia
yo
O gba ami-eye ti BAFTA, fun fiimu The Motorcycle Diaries lábé ìsoji awon fiimu ti ki i se ti ede Geesi,ni odun 2004..
wikipedia
yo
Lára àwọn iṣẹ́ rẹ̀ ni Love in the Time of Cholera, SyRiana, Quiz Show, àti The Legend of bagger Vance.Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀ òun ló ṣagbátẹrù àwọn fíìmù ìsàlẹ̀ lá, tó sì gbé won jáde.Fiimu Production Manager Location Management Second Unit Director or Assistant Director Loks Production Luru Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
atẹle ni atokọ ti awọn agbabọọlu ti o ti gba o kere ju igba awọn ibi-afẹde liigi ile ni bọọlu liigi Scotland ..
wikipedia
yo
David Wilson (tí wọ́n bí ní 17 December 1908, tó sì ṣaláìsí ní 22 February 1992) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì, tó gbá bọ́ọ̀lù fún Hamilton Académical F.C..
wikipedia
yo
Gẹgẹ bi i ọ̀kan lára àwọn ọmọ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù náà.Iṣẹ́ tó yàn làmáa jẹ́ ọ̀kan lára àwọn agbábọ́ọ̀lù tó máa ń goolu jù..
wikipedia
yo
O gba goolu 246 ni saa mokanla ki Ogun Àgbáyé Kejì tó wáyé..
wikipedia
yo
wọ́n sì yàn án gẹ́gẹ́ bí i agbábọ́ọ̀lù tó mọ́ ọn gbà jù.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Dumfries jẹ ọja aarin ilu, o si fìgbà kan jẹ ọja fun awọn ọlọ́lá ati lọ́balọ́ba ni Dumfries ati Galloway, ni Scotland, lẹ́bàá eti odo pépéd.ṣaaju ko to di ọba Scots, Robert The Bruce pa orogun re, ìyẹn Red Commyn ni Greyfrs Kirk, ní ilu ni odun 130..
wikipedia
yo
Young Pretender ní ilé-iṣẹ́ rẹ̀ ní agbègbè náà títí wọ òpin ọdún 1745..
wikipedia
yo
Nínú Ògùn àgbáyé kejì, àwọn ọmọ-ológun ti ìlú Norweg tó wà lẹ́yìn odi, ní Britain ló pọ̀jù nínú àwọn ọmọ-ológun Dumfries.ìtàn kò sí àlàyé rere nípa ìlú yìí, láti ìgbà tí wọ́n ti tẹ̀ ẹ́ do.díẹ̀ nínú àwọn àwọn òǹkọ̀wé kan gba péfries gbilẹ̀ bí ayé ìyàtọ̀ lákòkò iṣẹ́ Roman ti apá Ariwa ilẹ̀ Britain.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
International hockey Federation tí a gé kúru tí gbogbo ojú sí mọ́ sí fih, ó jẹ́ àjọ tó ṣe àmójútó eré bọ́ọ̀lù Alafigigbà ní orí pápá àti nínú yàrá ìyẹn ìyẹn is the (Field hockey) àti (Indoor Field ní́n)..
wikipedia
yo
Fih ni o n ma ri si awon idije ere boolu Alafigigba hockey ni agbaye, bi ti idije Ife Ẹyẹ agbaye hockey (hockey World Cup).Ìtàn wọn da fih sile ni ojo keje osù kìíní odun 1924 ni ​ Paris, Paul Likùny lo ajo yii kale, ti o si pada wa je aare fun ajo naa, lati se idahun si awon omo ere idaraya ere idaraya kan ti won ti won pe ni 1924 Olympics Olympics..
wikipedia
yo
Awọn ọmọ ẹgbẹ akọkọ ti wọn darapọ mọ awọn to da silẹ ni Austria, Belgium, Czechoslovakia, France, Hungary, Spain, ati Switzerland.Ni ọdun 1983, Fih darapọ mọ International Federation of Women's bẹrẹ Associations (Ifwha), ti won da sile ni ọdun 1927 nipasẹ Australia, Denmark, England, Ireland, Scotland, South Africa, the United States, ati Wales.Ile iṣẹ naa wa ni Lausanne, Switzerland lati 2005, ki won kuro nibe lo si Brussels, ni Belgium.Ni idahun si iṣẹlẹ to waye ni Russia ati Ukraine 2022 Russian invòjijì of Ukraine, Fih o gba Russia laaye lati kopa ninu 2022 Women's fih bẹrẹ Junior World Cup, ti wọn o si gba awọn alakoso Russian ati Bebára laaye si sise tabi eto fih KanStructure in Total, there are 140 member Associations within the Five Confederations Recogagod by Fih..
wikipedia
yo
This includes great Britain which is kórìíragniṣẹ́d as an adherent member of fih, the team was represented at the Olympics and the Champions Tro73..
wikipedia
yo
China girl jẹ fiimu odun 1987 kan, to kun fun ìwúlórí àti àhesọ, èyí tí abel Ferrara jẹ́ olùdarí fún, ti Nicholas St..
wikipedia
yo
John to je ojuse rẹ ko sile.Ìtàn China girl je fiimu kan to fe jo ti Romeo and Juliet..
wikipedia
yo
Ìlú Manhattan ní Ibùdó-Ìtàn, Ìtàn náà sì dá lé ọ̀dọ́mọkùnrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Tony láti ìlú Italy to yófẹ̀ẹ́ pẹ̀lú ọ̀dọ́mọbìnrin tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Tye, láti ìlú Chinatown..
wikipedia
yo
Àmọ́ àwọn ẹ̀bíkùnrin àwọn méjèèjì èèyàn láàárín ara wọn, tí kí Í ṣe kékeré.Isa Wọn gbé fíímù náà jáde ní September 25, ọdún 1987 ní Tí mẹ́ta mẹ́ta (193), wọ́n sì rí tó $362, lásìkò tí wọ́n gbé jáde.àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ọ̀gbẹlẹ̀ fún ìgbà pípẹ́ ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ti jásí ìparẹ́ àwọn igi, koríko àti ilẹ̀ tí a fín sin màálù tàbí gbin kan oko.Láti rí ilẹ̀ fún oko àti nkan ìsìn, àwọn ọlọ́kọ̀ àti dáràn dáràn ni wọ́n máà ngbìyànjú lati lọsi agbègbè tuntun èyí ló máà sábà jásí Moléjàganjàgan..
wikipedia
yo
Àwọn ọlọ́kọ̀ àti dáràn dáràn máa ń kópa nínú ìjà léléjàgan láti ọdún méjì sẹ́yìn èyí ló ti jásí ikú àwọn ènìyàn ẹgbẹ̀rún méjì ní ọdún 2018..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀ nínú àwọn ará abúlé ìpínlẹ̀ Plateau ni wọ́n kò fẹ́ kúrò ní agbègbè náà nítorípé wọ́n rí gẹ́gẹ́ bi ilẹ̀..
wikipedia
yo
Tí àlílí kan bá jọ, Bloec tuntun míràn ní wọ́n maa fi ìkànje àwọn ilé tó ti bàjẹ́ náà ṣe.Ọ̀gbẹlẹ̀ jẹ́ ìdálẹ̀ tó máa ń ṣẹlẹ̀ ní orílẹ̀ èdè Nàíjíríà tí ó sì maa maa gbogbo gbogbo orílẹ̀..
wikipedia
yo
Ní àríwá ilẹ̀ Ohunkan, Agbọ̀nfẹ́ ìṣẹ̀lẹ̀ ọ̀gbẹlẹ̀ ló ti wáyé tó sì já sí Iyán ní ọdún 1914, 1924, 1935, 1943, 1951–1954, 1972-1973, MorJónà 1989 and 1991-1995.iwadi bí ti àwọn Sutd, àwọn ilé iṣẹ́ Olùwáwádi ti ilẹ̀ Africa sọpé 79% àwọn agben ní ọ̀gbẹlẹ̀ àti ikun omi ti kóbá ní ọdún 2020..
wikipedia
yo
Lára wọn, 26.3% ṣé àjálù adikun nínú eré ọkọ wọn látara ojú ọjọ́ tíkò fararọ̀..
wikipedia
yo
ìwádí tí a pe àkọlé rẹ̀ ní “Àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà fẹ́ jẹun” sọ nípa àwọn ìpèníjà tí àwọn àgbẹ̀ Nàìjíríà àti àwọn tó kó oúnjẹ ṣe ìrìnàjò dojúkọ èyí tó sì le kópa àbójútó oúnjẹ orílẹ̀ èdè.Ipa ọ̀gbẹlẹ̀ tí jásí àlékún bá àyípadà nínú ojú ọjọ́ lágbàlágbà..
wikipedia
yo
Iwadi ọ̀gbẹlẹ̀ to ṣẹlẹ ni ọdun 1973 sọpé ọpọlọpọ eniyan ni wọn padanu emi wọn ninu iṣẹlẹ to si mu àdínkù ba iṣe agbe..
wikipedia
yo
Iwadi yi lofihan pe eniyan 10.3 Archlli ni apa Ariwa Naijiria lo koju iyan ti aimoye màálù si ku..
wikipedia
yo
Ni ọdún 1978, ìṣẹ̀lẹ̀ míràn wáyé tó jásí àdánù òun ọ̀gbìn bí àgbàdo àti sorghum látàrí ọ̀gbẹlẹ̀..
wikipedia
yo
àyípadà nlá ní ipa tí ọ̀gbẹlẹ̀ ko àríwá ilẹ̀ nàìjíríà láti ọdún sẹ́yìn tó sì kóbá oun ọ̀gbìn àti èrè ọkọ̀ ní agbègbè náà.Ọ̀gbẹlẹ̀ jẹ́ àdínkù tàbí àìrí rárá omi lórí ilẹ̀ látàrí àìrí ọjọ́ fún ìgbà pípẹ́ ní agbègbè náà..
wikipedia
yo
Eyi lo jasi ki oun ogbin ko kuna latari àìrí omi.Nigba ọ̀gbẹlẹ̀, agbara ero amunawa maa ndiku to si maa nko ipalara ba awon ise to gbẹkẹle.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Robert Lowe Mcphail (ọjọ karun-le-logun Oṣu Kẹwa Ọdun 1905 si ojo kerin-le-logun Oṣu Kẹjọ 2000) jẹ agbabọọlu alamọdaju ara ilu Scotland kan, ti o ṣere fun Ardrieonians, Rangers ati Aṣoju Scotland .Iṣẹ-airdri-Sans ti a bi ni Barrhead, Mcphail bẹrẹ iṣẹ rẹ ni ẹgbẹ Glasgow Junior Pollok ..
wikipedia
yo