cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ọpọlọpọ awọn ẹru to kopa ninu ija naa jẹ awọn alawọ dudu Ilu Afrika.itọkasi..
wikipedia
yo
ìsìnrú jẹ́ ohun tí àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n àtijọ́ míràn fi ọwọ́ sí, ó sì jẹ́ ohun tí ó farahàn nínú ìwé mímọ́..
wikipedia
yo
Àwọn ìwé àkọọ́lẹ̀ Amẹ́ríkà àti Britain àtijọ́ náà tún fọwọ́ sí ìsìnrú, pàápàá jù lọ, àwọn ìwé orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà kí ìjà abẹ́lé orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà ṣẹlẹ̀..
wikipedia
yo
Awọn kọkàn ti o fowo si ìsìnrú ma n tọka si Bibeli Mimọ, wọn gbagbo pe a bi awọn kọkan lati jẹ ẹrú, awọn miran si gbagbo pe ìsìnrú jẹ ohun ti a ti n ṣe lati iṣẹbayé.awọn itọkasi..
wikipedia
yo
Ìsìnrú jẹ́ ohun tí ó wọ́pọ̀ Griki láyé àtijọ́, bí ó ti wọ́pọ̀ ní àwọn àwùjọ míràn nígbà náà..
wikipedia
yo
Àwọn iṣẹ́ tí wọn ń lo àwọn ẹrú fún ni iṣẹ́ àgbẹ̀, iṣẹ́ Kuṣa àti gẹ́gẹ́ bí ọmọ ọ̀dọ̀ fún iṣẹ́ nínú ilé.Ní Griki àtijọ́, wọn kò ká ẹrù mọ́ ara àwùjọ ṣùgbọ́n wọn rí wọn gẹ́gẹ́ bí ohun ìní..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀ ẹrú kò létò lọ́wọ́ ara wọn, wọ́n sì wà lábẹ́ olówó wọn tí ó lè rà wọ́n, tà wọ́n, tabi yà wọ́n fún ẹlòmíràn.Ìgbìyànjú láti ṣe ìwádìí nípa ìsìnrú ni wolii àtijọ́ ti bá àwọn ìṣòro pàdé..
wikipedia
yo
Àwọn Àkọsílẹ̀ nípa ìsìnrú nígbà náà tako ara wọn, ọ̀pọ̀ wọn sì dá lórí ilẹ̀ Athens nìkan.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Oloye Daniel Conrad Taiwo (ti a bi ni ọdun 1781 ti o si fi ayé sílẹ̀ ni ọjọ́ ogún oṣù kejì ọdún 1901), àwọn ènìyàn tún mọ̀ọ́ sì Taiwo olówó..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ olùta ohun ìjà ogun, olówó àwọn ẹrú, àfifuni ati olórí àdúgbò kan nígbà tí ẹ̀kọ́ wà lábẹ́ ìjọba Britain.Ìpìlẹ̀ rẹ̀ a bí Táíwò olówó ní ọdún 1781 ní iṣIsheri, àdúgbò kan ní ìpínlẹ̀ Èkó..
wikipedia
yo
Baba rẹ̀, Oluwo̩, jẹ́ Ọlọ́fin Ìlú rẹ̀, ó sì fi ayé sílẹ̀ ní ọdún 1809..
wikipedia
yo
Olówó kó lọ sí ìlú Èkó ní ọdún 1848 ó sì jẹ́ ẹrù ogunmade fún ìgbà díẹ̀.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Okoro Idozuka je oludari ti 19th century ati jagun jagun ni agbegbe àròdizu, ile Naijiria..
wikipedia
yo
Arákùnrin náà jẹ́ olùjiròrò àgbà sí olùdásílẹ̀ abúlé Ndiakun Uno Arodi Arol..
wikipedia
yo
Okoro je gbajumo onisowo eru sise to lowo lowo.Igbe Aye Okoroï ni a si Bisi agbegbe Awka sugbon ti o ko losi arodi ni century..
wikipedia
yo
Arákùnrin náà padà yí orúkọ àbísọ rẹ̀ Bọ̀dá okoli sí ti aro..
wikipedia
yo
Okoro je baba fun Nwankwo Okoro.Okoro Izuka je okan lara awon oludari to pataki ni arodizu to si je eniyan jàkàn ni aro titi di eni.Ìnira ti Okoro dojukoni odun 1819, awon eniyan fi àìmọye esun kan Okoro lori jíjí awon eniyan gbe, eyi je ona lati ba owo arakunrin naa je..
wikipedia
yo
Láti ra iyì rẹ̀ padà, Okoro mu le, èyí jẹ́ ọ̀kan lára ìmùlẹ̀ méje tó tóbi jùlọ ní ayé igbana..
wikipedia
yo
Ìmùlẹ̀ yí ni èyí tí ẹni kẹ́ni tó bá fẹ́ mulẹ̀ máa ńṣe tí yó fi orí rẹ̀ búra fún àwọn òrìṣà ṣùgbọ́n tí yóò lo ayọmọ àwọn ẹni mẹ́fà tó Súmọ́ jùlọ..
wikipedia
yo
Ìmùlẹ̀ yìí lágbára tó bẹ́ gẹ́ tó jẹ́ pé tí ẹni náà bá jẹ̀bi ẹ̀sùn taa fíkán, àwọn òrìṣà yìí kò ní pa òun nìkan àfi kí wọ́n mú àwọn mẹ́fà tí wọ́n fikún ìmùlẹ̀ náà.Fún ti ìmùlẹ̀ tí Mázi Ọkọ̀li ìzuka fẹ́ ṣe, wọ́n ní kí ó fi àwọn mọ̀lẹ́bí sínú ìmùlẹ̀ náà àti gbogbo àwọn ọmọ ọkùnrin tí a Bísí ilẹ̀ Awanta.Nígbàtí Mazi Okoro IDzuka ṣetán láti ṣe ìmùlẹ̀ náà, ó wá àwọn ọkùnrin mẹ́fà ṣùgbọ́n ó kùnà a tirí ẹnì keje nínú àwọn ará ilé rẹ̀..
wikipedia
yo
Ameàmì yànda ọmọ rẹ̀ àgọ́si, èyí lọmú kí àwọn tó fi ẹ̀sùn kan Okoro jáwọ́ kúrò nínú ọ̀rọ̀ náà.Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ológun lọmọìtumọ̀ jẹ́ gẹ́gẹ́ bí ọba Èkó láti 1780s títí di ọdún 1803..
wikipedia
yo
Òun ló jẹ lẹ́yìn Ọba Elétù Kékeré, ẹni tí ó wà lórí oyè láti ọdún sí 1775 and 1780..
wikipedia
yo
Ológun Lédèkà jẹ́ ọmọ erelú Kuti, ẹni tí ó jẹ́ ọmọ ọba Adó, àti Alaagba (’fẹ́ni' ẹni tí ó jẹ́ ọmọ Ìjẹ̀ṣà àti olùbádámọ̀ràn ọba Akinsemoyin.Ìtàn rẹ̀ lọmọbaba Sdunrẹ̀ babaláwo ní ìpínlẹ̀ èkó ẹ̀kọ́ nígbà àwọn ọdún 1700s..
wikipedia
yo
Nígbà tí lọ́rọ̀re wà lórí oyè, ìbára láàrín ẹ̀kọ́ àti and Ìjẹ̀bú wọ́pọ̀ sí, àwọn Ìjẹ̀bú gbé oúnjẹ wá láti gba iyọ̀, tobacco, spirits, àti àwọn ìkan míràn ti àwọn ẹ̀kọ́ gbà lọ́wọ́ àwọn ara ẹrú ti orílẹ̀ èdè Portugal..
wikipedia
yo
Sberere ni omo tọ́pọ̀, awon bi;hinlókun, adelé Àjọsun, Akitóyè, Akiolu, Olukoju, ati Olusisi.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
níara Bely © -1879) tí a mọ̀ ní gbájúmọ́ gẹ́gẹ́bí Elizabeth Bailey Gómez jẹ́ olórí ti ṣọ́ṣọ́-ilẹ̀ Áfríkà jẹ́ oníṣòwò pàtàkì ni Century ti ọ̀kan dínloGum..
wikipedia
yo
Arabinrin na jáfáfá lori owo oko ẹru sise ni FArenya, ile Guinea.itan igbesi aye niAraniara Bely je ọmọbinrin Emmanuel Gómez, oludari ti bakia ti ṣọ́ṣọ́-ilẹ Afrika ni ile Guinea..
wikipedia
yo
níara kawe ní Liverpool.Ní ọdún 1809, níara fẹ́ oníṣòwò ẹrú Sdira Edward lightBourn níbi tí wọ́n kọ́kọ́ gbé ní Bangalan..
wikipedia
yo
Ó bẹ̀rẹ̀ síni gbé ní ilé alájà méjì èyí tó máa ń pe NK àfin..
wikipedia
yo
Agbegbe yi di abule nigbati Bely bẹrẹ iṣẹ ọwọ ọkọ ẹru, eleyi pada di ọna ọwọ sise lati oke ti foUta Djalon.Ni ojo meta dinlogun, osu January, odun 1852, ijoba ile British ati Sierra Leone pelu apapọ oludari Abule fagile owo oko eru sise ni agbegbe naa..
wikipedia
yo
Mary òmìnira (oníṣòwò ẹrú) rí àyípadà yí géẹ́ ìpalára fún ọwọ́ rẹ̀ parapọ̀ pẹ̀lú níara bẹ̃ly àti Charles láti lòdì sí ifagile náà ni odò tó wà ní ìsàlẹ̀ ti ṣúṣú.Ìjà yí ni kògbé òmìnira, Bely àti Wilkinson ní ọdún 1855..
wikipedia
yo
Àkókò yí ni ọwọ́ oko ẹrú ṣíṣe di àfìsẹ̀yìn eleyĩ ló mú kí àwọn olówò ọkọ̀ ẹrú bẹ̀rẹ̀ òwò míràn.Ikú níArani ọjọ́ mẹ́fà dínlógún, oṣù April, ọdún 1879, níara Bely kú èyí tó jẹ́ ti òjìji lẹ́yìn tí wọ́n sí mímọ́ ní ìjọ Anglican gẹ́gẹ́bí ọ̀rọ̀ ọ̀kan lára àwọn olùbágbé rẹ̀..
wikipedia
yo
Ni akoko, a sin níara si abẹ́ igi cheese ni arin Abule sugbon ni ọdun 1966, won gbe sare si agbegbe naa ti won sin oku re si .itọkasi..
wikipedia
yo
N'gangue M'vobe niamambi je oba ijoba loang ni awon odun to gbeyin odun 1600s..
wikipedia
yo
O ri opo ere ninu tita awon eniyan gege bi eru fun orile ede [[Kingdom of Portugal|Portugal]
wikipedia
yo
GẸ́GẸ́ BÍ ÀKỌSÍLẸ̀ Olfert Dupper, NIAMBÍ NÍ Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ohun ìjà ogun, BÍ O tile je wipe ko mo bi a se n lo won.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
CAty jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ènìyàn jàkàn ní agbègbè ti Gorée.caty Louette jẹ́ ọmọbìnrin arákùnrin tó wá láti ilẹ̀ French Nicolas Louet, tó jẹ́ òṣìṣẹ́ ilẹ̀ French ti East India àti mistress rẹ̀ caty de Rufícasal ti Gorée.àgbọ̀nrín di signanare-sort ti Pierre AusSéSéc de Carcas ti ilẹ̀ French, òṣìṣẹ́ ti East India ti ilẹ̀ French..
wikipedia
yo
CAty lè kọ́ àti ka, èyí ló mú kó jẹ́ obìnrin tó lọ́wọ́ gidi gan tó sì ní ọkọ̀ ẹrú tó tóbijùlọ ní gbógun.caty ní ẹrù 68 níbi àwọn oníṣòwò ẹrú tí ma ń nta àwọn òsọ wọ́n fiwon pamòkasí..
wikipedia
yo
fẹ̀nda Lawrence (1742 - Lẹ́yìn 1780), jẹ́ olóko ọ̀wọ́ ẹrú Áfíríkà tí ó ṣiṣẹ́ yìí ní sálọum, ìlú Kurka.ìtàn ayé TOEminda Lawrence gbé lẹ́gbẹ̀ẹ́ Odò Gábíàbíà ní àwọn ọdún 1700s..
wikipedia
yo
Ní àdúgbò náà, ó jẹ́ olùbádúdún dúrà láàrin àwọn oníṣòwò Britain, France àti àwọn oníṣòwò Áfíríkà..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1772, Lawrence lọ sí AkinTeen Coloes ti America láti dáwọn..
wikipedia
yo
Nígbà yìí, ó ti yapa láti ọ̀dọ̀ ọkọ Òyìnbó tí ó fẹ́.Nígbà tí ó wọ ọkọ̀ ojú New Britannia, Lawrence mú ẹrú márùn-ún pẹ̀lú ara rẹ̀..
wikipedia
yo
Ọkọ naa DeCharleston, South Carolina, lẹ́yìn ọjọ́ méjìdínlógójì tí ó gbéra..
wikipedia
yo
Adari oko naa, Stephen Deane, si tele Lawrence lọ si Georgia.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ìpalára jẹ́ ìsẹ́ni-láìdá búburú ní ara, tí ó lè ba ayé irú ẹni bẹ́ẹ̀ jẹ́ tàbí wíwà láyé irú ènìyàn bẹ́ẹ̀..
wikipedia
yo
A tún lè ṣe àpèjúwe rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìbánilára jẹ́ tí ó le dín iyì ohun kù, burẹ́wà ohun bẹ́ẹ̀, àìlèṣe rẹ̀, tàbí kí ó sọ irú ohun bẹ́ẹ̀ di aláìpé..
wikipedia
yo
Ní ayé ode-oni, ẹ̀rọ yìí dásẹ̀ sí ohun tí ó buru jáì.aka-ọ̀rọ̀ ní 2019, Michael H..
wikipedia
yo
Stone, Gary Bruàfarawé, àti Ann Burgess dábàá ìlànà àìtè láti lè ṣeyàtọ̀ “ìpalára” àti “Ìyá”, nítorí gbígbé àwọn ọ̀rọ̀ wọ̀nyí síra máa ń sábà wáyé..
wikipedia
yo
wọ́n sì dábàá pé ìyákúrò níṣẹ́ pẹlu “ìyọkúrò patapata, lọ́nàkọnà tó bá gbà, apá ńlá kan lára àlàyé tabi òkú, ní pàtó, orí irú ẹni tabi òkú bẹ́ẹ̀, apá, ọwọ́, ìbàdí, ẹsẹ̀, tabi àtẹ̀léẹsẹ̀”
wikipedia
yo
Nígbà tí ìpalára lọ́nà mìíràn ẹ̀wẹ̀ níṣẹ́ pẹ̀lú “ìyọkúrò tàbí ìbàjẹ́ àìní-àtúnṣe lọ́nàkọnà àwọn ìpín ara ńláńlá ènìyàn tó wà láàyè tàbí tó ti kú..
wikipedia
yo
Ó lè jẹ́ yíyọ kóró-ẹpọ̀n, àwọn ẹ̀yà ara inú, tàbí yíya àwọn“
wikipedia
yo
Nípasẹ̀ àwọn ìlànà wọ̀nyí, yíyọ ọwọ́ ènìyàn pátápátá máa túmọ̀ sí “ìyọkúrò”, nígbà tí ṣíṣe ìjàmbá fún ìka-ọwọ́ yóò jẹ́ ìpalára, ti yíyọ gbogbo òkè ara títí dé ẹsẹ̀ yóò jẹ ìyákúrò, nígbà tí yíyọ tàbí ṣíṣe ìjàmbá fún ọyàn tàbí àwọn ẹ̀yà-ara mìíràn yóò jẹ́ ìpalára.Ìpalára gẹ́gẹ́ bí i ìfìyàjẹ ènìyàn James Gavin ti Douglas, Lanibùgbé jẹ́ èyí tí etí rẹ̀ di gígé sọnù nítorí ó kọ̀ láti ṣe ìkọ̀sílẹ̀ ìgbàgbọ́ ẹ̀sìn rẹ̀..
wikipedia
yo
Ní orílẹ̀-èdè Japan, Ggon Garcia àti àwọn ará rẹ̀ jìyà irú ìfìyàjẹ yìí.Bákan náà, ni agbègbè-agbára àwọn kòló mẹ́tàlá, fún ẹ̀sẹ̀ kéékèèké bí i tí ènìyàn kan bá jí Ẹlẹ́dẹ̀ gbé lè fa kí wọ́n la etí irú ènìyàn bẹ́ẹ̀ tàbí kí wọ́n gé bọ̀, ìgbà mìíràn sì wà tí ìfìyàjẹ fún ẹni tó bá ń ṣe àtúnrọ àwọn ohun ni láti sọ irú ẹni bẹ́ẹ̀ sínú epo tó bá wà lórí iná, àpẹẹrẹ ìpalára ìwọ̀-oòrùn nìyí.Síwájú sí i, òmìnira kò digi túmọ̀ ilẹ̀ Amẹ́ríkà kú..
wikipedia
yo
Bí àpẹẹrẹ, ní agbègbè gúúsù-mọ́-ìlà-oòrùn (ilẹ̀ Tennessee), àpẹẹrẹ ìdájọ́ àìfilélẹ̀ kíkan lábẹ́ Cuẹ̀ka Manda wáyé ní 1793 nígbàtí adájọ́ John McNairy ṣe ìdájọ́ fún olè ẹ̀sìn àkọ́kọ́, John McOjúd Jr., pé kí wọ́n so orí àti ọwọ́ rẹ̀ mọ́ igi ẹlẹ́wọ̀n kan fún wákàtí kan fún ẹ̀gbà kakadínlógójì, wọ́n sì tún gé etí rẹ̀ méjèèjì kúrò, lẹ́yìn náà ni wọ́n kọ lẹ́tà "H" àti "T" sí èké rẹ̀ méjèèjì.Gẹ́gẹ́ ahọ́n burú jáì, ṣùgbọ́n kò wọ́pọ̀ gẹ́gẹ́ bí i oríṣi ìpalára àti ìfìyàjẹ..
wikipedia
yo
Nítorí ahọ́n ni ọ̀pọ̀ àwọn ohun-èlò ẹ̀jẹ̀, ẹ̀jẹ̀ dídá yóò pọ̀ Olùjìyà bẹ́ẹ̀ sì le tipa rẹ̀ kú..
wikipedia
yo
Nénene YoJohannesburg, tí ó jẹ́ olùgbéjó aláìyẹ fún olùjọba ìtẹ́ Ethiopia jẹ́ èyí tí etí rẹ̀ méjèèjì àti imú rẹ̀ di gígé sọnù, lẹ́yìn náà ni wọ́n tú sílẹ̀.àmúlò irúfẹ́ ìpalára fún àwọn olùgbéjọ aláìyẹgé ìtẹ́ ọba yìí ti wà láti àìmọye ọdún sẹ́yìn ní agbègbè àárín-ìlà-oòrùn..
wikipedia
yo
nítorí láti tayọ gẹ́gẹ́ bí ọba láyé ìgbà náà, irú ẹni bẹ́ẹ̀ gbọdọ̀ wà ní pípé..
wikipedia
yo
Irú ìpalára àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ yìí ] wáyé kí ó le jẹ́ àríkọ́gbọ́n fún àwọn ẹlòmíràn.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Akitóyè (Ku lọ́jọ́ kejì Oṣù Keta-an Ọdún 1853), tí ọ̀pọ̀ ènìyàn máa ń ṣìpẹ̀ nígbà mìíràn ní akíntóyè, jẹ́ ọba Èkó ní ètòẹ́; Ó kọ́kọ́ jọba láti ọdún 1841 sí 1845, lẹ́yìn náà, ó tún jọba láti ọdún 1851 sí 1853..
wikipedia
yo
Bàbá rẹ̀ ni ọba ológun nítòòsíre, àwọn àbúrò rẹ̀ sì ni àwọn ọba aládé ọ̀sìnlókùn àti adelé Àjọsun.Bí ó ṣe jọbáwọn pa ọba Oluwo̩lé ọdún 1841 nígbà tí ara kan san tí nǹkan bí àgbà ìbọn kan sì bẹ ní ààfin ọba..
wikipedia
yo
Àwọn afọbajẹ ìbá ìránṣẹ́ pe ọmọba Kosoko láti wá gorí ìtẹ́ baba rẹ̀, ṣùgbọ́n kò sí ẹni tí ó mọ ibi tó wá..
wikipedia
yo
Yàtò sí èyí, ìjà láàárín Elétù Òdìbò àti Kòsómò Fárù tí ẹlẹtù fí dènà Kòsọ́kọ́ láti joba..
wikipedia
yo
Nítorí ìdí èyí, wọ́n fi Akitóyè, ẹni tí ó jẹ́ àbúrò bàbá Kosoko ati àbúrò sí ọ̀sìnlókun jọba ẹ̀kọ́..
wikipedia
yo
Akíkanjú oníṣòwò àti Olówó ẹrú, Madam Tinubu, tí ó ti kọ́kọ́ fẹ́ adelé lóko gbárùkù ti àbúrò ọkọ rẹ̀, akítóyè láti jọba dípò Kosoko.Bí Kosoko ṣe lé akítóyè kúrò lórí oyèàwọn olóyè, pàápàá jù lọ Elétù Òdìbò gbìyànjú láti tako ilá kàkà akítóyè láti parí ìjà pẹ̀lú àbúrò bàbá ẹ̀, ṣùgbọ́n kò gbà, ó fi àìmọ̀kan rẹ̀ parí ìjà náà pẹ̀lú Kosoko, ó sì pàṣẹ pé kí Kosoko padà sí ìlú Èkó..
wikipedia
yo
Kosoko wọ ọkọ̀ ojú omi ti gbajúmọ̀ olówó ẹrú, José Domingo Martínez padà sí ìlú Èkó..
wikipedia
yo
Akitóyè gbiyanju lati tu Kosoko lóju pelu orisirisi ebun, kódà, o da a lola oye nipa fifi i je oye yo ti Ereko..
wikipedia
yo
Kosoko yára lo ànfààní yìí láti láti wá ojú rere àwọn olóyè ajagun, àti àwọn ará ìlú tí wọ́n jẹ́ Mùsùlùmí..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó ya, gbajúmọ̀ ti Kosoko gbajúmọ̀ láàárín àwọn Olóyè sí ní kò alábá alátúgun nínú, loof idi èyí, ó gba ìlú Badagry; lọ.. lọ..
wikipedia
yo
Èyí kò tẹ́ Ọba Akitóyè lọ́rùn, bẹ́ẹ̀ ló pàṣẹ fún Elétù Òdìbò láti padà sí Èkó, èyí bí Kosoko nínú, ó sì pinnu pé bí Elétù Òdìbò bá padà sí Èkó, òun yóò dé ara òun ládé, tí òun yóò sì jọba.Wàhálà yìí bẹ́ sílẹ̀ láàárín Ọba Ákíyeye àti ọmọba Kosoko..
wikipedia
yo
Lásìkò náà, Kosoko rán aláago rẹ̀ láti kéde káàkiri ìgboro Èkó pé “Kí wọ́n kìlọ̀ fún màjèsín tí wọ́n fi jọba láàfin pé kò ṣọ́ra rẹ̀, pé bí kò bá ṣọ́ra, yóò jìyà, yóò wẹ̀wẹ̀ ẹ́ ya”
wikipedia
yo
Akitóyè naa ko gbenu ro, oun naa ran alaago re pe ko lo kede ikilọ pe, "A ti ti oje bo ọlòwasa lọwọ, ko si baba ẹni ti o le bo o"
wikipedia
yo
Inú bí Kosoko, ó sì fèsì pé, ó ṣì fèsì pé bí òjé ò bá sẹ́ ẹ bó, òun yóò gẹ̀ ẹ́".rògbòdìyàn yìí mú Kosoko àti àwọn wíw rẹ̀ dá wàhálà ogun olómirọ sílẹ̀ n'ìlú Èkó lọ́dún..
wikipedia
yo
Àwọn ọdún Kosoko kógun ja ọba Akitóyè láàfin rè̩ fún ọ̀sẹ̀ mẹ́ta..
wikipedia
yo
Ogun yìí pọ̀ tó bẹ́ẹ̀ tí akítóyè fi sálọ gba orí omi ọ̀sà, lápá àríwá gba etí omi àgbọ́yí pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ ọ̀ṣọ́di Tápà, tí ó jẹ́ balogun Kosoko..
wikipedia
yo
Oshodi tàpá parọ́ fún Kosoko pé lọ ìṣújú fún àwọn ọ̀tá rẹ̀ láti sá lọ..
wikipedia
yo
Akitóyè kọjá sí Abeokuta, níbi tí wọ́n ti gbà á láàyè láti ṣe àtìpó..
wikipedia
yo
Ìbẹ̀rù Akitóyè mú Kosoko, ó sì pàṣẹ fún àwọn Ẹ̀gbá láti gé orí akítóyè wá fún òun, ṣùgbọ́n àwọn Ẹ̀gbá kọ̀..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó di ọdún 1845,àwọn Ẹ̀gbá ran akítóyè lọ́wọ́ láti sá lọ sí Badagry, ìlú àwọn ogúnléndé àwọn ọmọ èkó..
wikipedia
yo
Awon oyinbo ajíyìnrere ijo Anglican ni Badagry ati awon onisowo ilu Egba ati geesi ti won o fe idiwo fun owo won di pàǹpà po, won si ran Akitóyè lowo nílùú Eko..
wikipedia
yo
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ìgbìyànjú akítóyè láti tako fífi òpin sí okóòwò ẹrú jẹ́ ìwà ìmọtaraẹninìkan, èyí tí ó tako Òyìnbó ọ̀rẹ́ rẹ̀ ará ìlú Gẹ̀ẹ́sì, Domingo Martinez, tí ó ti fìgbà kan ràn án lọ́wọ́ láti gba ipò ọba rẹ̀ padà ṣùgbọ́n tí kò ṣeé ṣe lọ́dún 1846.Lọ́jọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 1851, ọjọ́ tí wọ́n ti wá sọ di ọjọ́ ìkógun ja ẹ̀kọ́ tàbí ọjọ́..
wikipedia
yo
Ọjọ́ burúkú ni ọjọ́ náà, ọba Kosoko sa gbogbo agbára rẹ̀, ṣùgbọ́n pàbó ló jásí, nígbà tí ó di ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kejìlá ọdún 1851,ogun yìí, tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí ogun ahóyaya tàbí ogun agidingb borí Kosoko, tí Kosoko àti àwọn ọmọ ogun rẹ̀ sálọ sí Ìjẹ̀bú..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn èyí, wọ́n dá Akitóyè padà gẹ́gẹ́ bí ọba ìlú Èkó lẹ́ẹ̀kejì..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó di ọjọ́ kìíní oṣù kìíní ọdún 1852,akítóyè fọwọ́ sí ìwé àdéhùn láàárín ìjọba ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì àti ẹ̀kọ́ láti fòpin sí okóòwò ẹrú.Ikú àti ipa rẹ̀Akitóyè kú lọ́jọ́ kejì Oṣù Kẹ̀sán-an Ọdún lẹ́yìn ikú rẹ̀, ọmọ rẹ̀ doṣùko jọba..
wikipedia
yo
Ṣugbọn Jean Kẹ́gavits ní tirẹ̀ lérò pé Akitóyè pa ara rẹ̀ ni nígbà tí ó rí i pé gbajúmọ̀ òun ń dínkù nílùú Èkó, ati pé nígbà tí ó rí i pé òun kò lè mú àdéhùn tí ó bá àwọn òyìnbó ṣe ṣe dójú àmì .láti ṣe ayẹyẹ Ìrántí Ikú rẹ̀, wọ́n gbé ẹyọ àkọ́kọ́ jáde ní Èkó..
wikipedia
yo
ọmọọmọ Akitóyè, Ibikunle Akitóyè jọba ẹ̀kọ́ láti ọdún 1925 sí 1928.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Iṣowo ẹru niAtlantic tàbí Transatsára slave trade jẹ́ tàbí ìgbà tí àwọn oníṣòwò ẹrú bá gbé àwọn èèyàn aláwọ̀ dúdú kúrò gẹ́gẹ́ bí ẹrú láti Orílẹ̀ Áfíríkà lọsi Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Àwọn ará Yúróòpù wọ́n á máa lo ọkọ̀ ojú omi ẹrù tí wọ́n fi ń ṣe òwò ẹrú máa ń lo ọ̀nà ìṣòwò onígun mẹ́ta àti àrin àárín inú Atlantic déédéé, ó sì wà láti ọ̀rúndún kẹrìndínlógún sí Sétúrì kọ́kàndínlógúnpúpọ̀ jùlọ nínú àwọn tí wọ́n gbé lọ fún ìṣòwò ẹrú nípasẹ̀ Transatsára jẹ́ àwọn ènìyàn láti àárín Africa àti ìwọ̀-oòrùn Africa tí àwọn oníṣòwò ẹrú tí Ìwọ̀-Oòrùn Áfíríkà ti tà sí àwọn oníṣòwò ẹrú bíi àwọn Portuguese, British, Spanish, Dutch, àti Faransé tí àwọn náà n ta ẹrú..
wikipedia
yo
Nígbà tí àwọn mìíràn tí wọ́n mú tààrà nípasẹ̀ àwọn oníṣòwò ẹrú ní àwọn ibi ogun létí òkun; àwọn oníṣòwò ẹrú ní ilẹ̀ Yúróòpù kóra jọ, wọ́n sì fi àwọn tí wọ́n wá lẹ́rú sẹ́wọ̀n láwọn ibi olódi ní etíkun Áfíríkà, wọ́n sì kó wọn wá sí ilẹ̀ Amẹ́ríkà.Àyàfi àwọn ará ìlú Portugal, àwọn oníṣòwò ẹrú Yúrópù ní gbogbogbò kò kópa nínú àwọn ìkọlù nítorí ìrètí ayé fún àwọn ará ìlú Yúrópù tí wọ́n wà ní ní ìhà ìsàlẹ̀ aṣálẹ̀ Sàhárà, èyí wáyé láàrin ọdún kan láàárín àkókò ti ìṣòwò ẹrú (èyítí ó jẹ́ ìṣáájúu ní gba ti ààrùn ìba wà ní jákèjádò tí wọ́n sì fi quinine ṣe ìtọ́jú ìba náà.Àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n wà ní apá Gúsù Atlantic àti ìletò Carri-án gbáralé àwọn ẹrú fún ètò ọrọ̀-ajé wọn àti àwọn iṣẹ́ oríṣiríṣi èyí tí iṣẹ́ Ìrèké àti àwọn ohun ọ̀gbìn mìíràn mìíràn wà níbẹ̀ níbẹ̀..
wikipedia
yo
Èyí ni àwọn ará ilẹ̀ ilẹ̀ ìwọ̀ oòrùn YORÙ wò pé ó jẹ́ ohun pàtàkì tí wọ́n sì ń bá àwọn orílẹ̀ èdè mìíràn ní òpin 17th àti 18th ajeẹ́ńtúrì, tí wọ́n ń bá ara wọn jà láti ṣẹ̀dá ìjọba tí ó ga jùlọ lórí àwọn ìlú òkèrè (ìgbàìnpù Empire). abẹ́lẹ̀..
wikipedia
yo
Jumbes tí Nektakòta jẹ́ àkójọpọ̀ àwọn onísí ilẹ̀ Lárúbáwá-Swahili tí wọ́n gbé ní Nọṣẹ́ta, ìwọ̀ oòrùn tí Ibùdó ti Malawi..
wikipedia
yo
Iṣe wọn ni ki wọn ma fi aṣọ gba Ivory ati ẹru ni etikun ti Swahili..
wikipedia
yo
Àwọn oníṣòwò yí ló gbé ẹ̀sin Mùsùlùmí àti àṣà rẹ̀ wá sí agbègbè Nistakòta tí wọ́n sì tún jẹ́ ẹni àkọ́kọ́ láti gbin ìrẹsì àti agbọ̀n ní agbègbè náà.Ìtàn dynasty náà ni Salim bin AbdAllah wá sì N Hanata ní ọdún 1840..
wikipedia
yo
Arákùnrin náà jẹ́ Lárúbáwá láti Zanzibar tó sì kópa nínu owó ẹrú àti Ivory ni Ujiji àti Tabora ta pé ní Tanzania ní ayé ìnilén sọfún àwọn ìjòta ìlà ti Gbali kí wọ́n fún òun ní ilé fún owó ṣíṣe..
wikipedia
yo
Ó kópa láti lágbára ní agbègbè náà láti kó dhow èyí ló mú kí àwọn oníṣòwò láti tajà lórí odó àti pé ńtorí arákùnrin náà ni òun ìjà, èyí ló jẹ́ kí ó lè dábọ́bò àwọn ará odò náà láti ọwọ́ ìjà àwọn NGO.Ní ara JÙmbe mà ma ń rà 20000 ẹrù lọ́dún lósì ibùdó Kilwa ní Tanzani ayé ìsìn..
wikipedia
yo
Àwọn tí wọ́n kó lẹ́rú ni wọ́n ma ńfi pamọ́ sí Aramuọṣẹ́takòta títí di ìgbà tí wọ́n !Pé ẹgbẹ̀rún kan..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn náà ni wọ́n ma kó wọn sí ọkọ̀ ojú omi Malawi ti wa sí i pa múwọn láti rìn fún oṣù mẹta tabi mẹrin títí wá fi dé Ọjà Oko Ẹrú Kilwa níbi tí wa ti tà wọ́n..
wikipedia
yo
Missionary David Livingstone rí ọkọ̀ ẹrú yí nígbà tó wá sí Arauntakòta ní ọdún 1861..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1864, jùmbes ṣe treaty pẹ̀lú àwọn ará jùmbe àti olóyè Chew láti fi ní bá oko ẹrú..
wikipedia
yo
Èyí jásí pàbó tó sì mú kí oko ẹrú tẹ̀síwájú.Àwọn Jũmes tú má ńṣe ọkọ̀ ọwọ́ Ivory..
wikipedia
yo