cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Apostolic Vicar Joanny thevenoud ni ó kọ́ ìjọ náà láàrin àwọn ọdún 1930s, nígbà tí àríwá Áfríkà sì wà lábẹ́ ìdarí orílẹ̀ èdè France, wọ́n sí ilé ìjọsìn náà ní ọjọ́ kàndínlógún oṣù Kínní ọdún 1936, lẹ́yìn tí wọ́n fi ọdún méjì kọ́.Àwọn ìtọ́kasí Burkina Faso..
wikipedia
yo
Je nkan ti o ṣẹlẹ laarin awọn ọdun 1950s si 1975 nigba Cold War, ti ọpọlọpọ orilẹ ede si gba ominira..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìṣẹ̀lẹ̀ yìí ló mú wàhálà àti àìsímin dání, díẹ̀ nínú wọn ní Ìlúbo Ìlúp Dllion ní British Kenya, Algerian War ní French Algeria, Congo Crisis ní Belgian Congo, Angolan War of independence ni Portuguese Angola, Zanzibar Revolution ni Sultanate of Zanzibar, ati Ogun Abele Nàìjíríà ti Biafra ati Ìjọba Nàìjíríà jà.Bí àwọn orílẹ̀-èdè náà ṣe gba òmìnira tabili yí sọ bí àwọn orílẹ̀ èdè méjìdínlọ́gọ́ta ṣe gba òmìnira.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Emirate of say jẹ́ ilé mùsùlùmí kan ti Alfa Mohamed Dibobo, adarí Qadiriyya Súfì kan dá kalẹ̀ ní ọdún 1825, Mohamed wá sí say àti Ddnne ( ní Málì) ní ọdún Oyinon..
wikipedia
yo
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé dibobo kìí ṣe Akọgun wọ̀lú, ó sì láṣẹ lórí say nítorí pé ó jẹ́ Alfa àti pé ó wà lára àwọn tí ó dá abo bo ṣòkòtò Empire, tí àlùfáà Q.)” Súfì, Usman Dan fodio kalẹ̀.Nígbà tí ó sì gbajúmọ̀, Emirate of say jẹ́ ibi tí àwọn ènìyàn mọ̀ láti gao dé Gbo gẹ́gẹ́ bí ibi tí wọ́n ti ń kọ nípa ẹ̀sìn Islam..
wikipedia
yo
Àwọn adarí ìlú say láti ọdún mọdún jẹ́ àwọn ìran díbóbò..
wikipedia
yo
Àwọn ni; Alfa Mohamed Diou (1825—1834), Boubacar Mobobo (1834–1860), Abdoura (1860-1872),láyé (1872-1874), Abdoulwagdou (1874-1878-1878), Saroko Alfa Baba (1878-1885), Amadou Satoohun Modibo (1885—1893), Halirou Abdo-apmo (1893—1894). Àwọn ìtọ́kasí itan ile Afrika..
wikipedia
yo
Agbara omi Namibia ti ọdun 2008 waye ni ibẹrẹ fẹburari 2008, eyi ti o fa agbara ojo nla fun bi aadọta ọdun...
wikipedia
yo
Agbára ọjọ́ náà pa ènìyàn tó ń lọ bíi méjìléní ní ìbẹ̀rẹ̀ oṣù kẹta,pẹ̀lú àpapọ̀ ènìyàn tó lé ní 65,000 tí wọ́n farapa, ní agbègbè Tolaàtiàti, oshikòtò, OsHana, óhangwena àti carcici..
wikipedia
yo
Èrò lápọ̀jù àti àìní ìmọ́tótó ló fa ìmójútó ní káàmpù..
wikipedia
yo
Ọ̀gọ̀rọ̀ ènìyàn tó wà ní Kampù náà ṣàkóbá bá ètò-ìlera ní ibẹ̀, ìtànkálẹ̀ àrùn ìbá sì wáyé, èyí tí wọ́n kéde ní oṣù kẹta..
wikipedia
yo
Ni ojo kerinla osu keta, ajo United Nations Office for Outer Space Affairs ke si International Charter for "Space and Major Disasters".Àwọn ìtọ́kasí Namibia..
wikipedia
yo
African Union (au) pín àwọn orílẹ̀ èdè tó jẹ́ ara rẹ̀ sí márùn-ún..
wikipedia
yo
Wọ́n ti ka àwọn ọmọ àwùjọ Afrika, èyí tó jẹ́ àwọn ọmọ Afrika ṣùgbọ́n tí wọ́n ń gbé ní orílẹ̀ míràn bí Amẹ́ríkà, Australia, Asia, àti Europe, gẹ́gẹ́ bí agbègbè Africa Union kẹfà.Àtòjọ àwọn agbègbè Africa unionarutúnguila oorurin Oorunari ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Àwọn orílẹ̀ èdè márúnlédọ́ta ni wọ́n jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ African Union (au)..
wikipedia
yo
Au jẹ́ ẹgbẹ́ tó Ropoorga] of African Unity (OAU), àyè sì sí ní Au láti gba àwọn tó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ OAU.Nígbà tí ó ṣe má di ọdún 2017, Àjọ Au ti dé gbogbo orílẹ̀ èdè ní Afrika, yàtọ̀ sí àwọn ilé Spanish North Africa ti CeUta, Melilla, àti Velez de la Gomera.Iye olùgbé àwọn orílẹ̀ èdè Au jẹ́ 1,0,68,000,000 (ní ọdún 2013)Àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Africa UnionÀwọn ọmọ ẹgbẹ́ òrùn Union tẹ́lẹ̀.. Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ìyípadà ojú-ọjọ́ ni South Africa ń yọrí sí àwọn ìwọn òtútù tí ó pọ̀ sí àti ììyípadà ọjọ́..
wikipedia
yo
Ẹ̀rí fi hàn pé àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ojú ọjọ́ tó burú jáì túbọ̀ ń di olókìkí nítorí ìyípadà ojú ọjọ́..
wikipedia
yo
Eyi jẹ nkan ìdàmú pataki fun awọn ọmọ orilẹ-ede South Africa nitori iyipada oju-ọjọ yoo ni ipa lori ipo gbogbogbo ati alafia ti orilẹ-ede naa, fun apẹẹrẹ pẹlu n ṣakiyesi awọn orisun omi..
wikipedia
yo
gẹ́gẹ́ bí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ẹ̀yà mìíràn ti àgbáyé, ìwádìí ojú-ọjọ́ fihàn pé ìpèníjà gidi ni South Africa ni ìbátan díẹ̀ síi sí àwọn ọ̀ràn àyíká ju àwọn ìdàgbàsókè..
wikipedia
yo
Ipa ti o lágbára julọ yoo jẹ ifọkansi ipese omi, eyiti o ni awọn ipa nla lori ẹka iṣẹ-ogbin..
wikipedia
yo
Èyí wà ní apákan ńlá nítorí ètò agbára rẹ̀ tí ó gbẹ́kẹ̀le èédú àti epo..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bi apákan ti àwọn àdéhùn àgbáyé rẹ̀, South Africa ti ṣe àdéhùn láti gba àwọn ìtújáde laarin 2020 àti 2025.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Yàtò sí èdè Arabic ti wọn n sọ, àwọn eniyan bíShari tún n sọ beja language, èdè ti o jẹ ara àwọn ìdílé Afroásìati.Ibi tí wọn gbé àwọn ẹya biShari gbé ní aṣálẹ̀ nuBian ni Sudan ati apá gúúsù Egypt..
wikipedia
yo
Wọ́n gbe ní ataiju (tabi Atbáì) laarin ọdọ nílẹ̀ àti Red Sea, Ariwa Amarar àti Gúúsù Ibi tí àwọn Ènìyàn Ababdá wà, laarin aṣálẹ̀ Nọla ati pẹ̀tẹ́lẹ̀ nílẹ̀, ibẹ̀ ni ọpọlọpọ òkúta ati àpáta.Iye àwọn tó jẹ́ ẹ̀yà náà tó ẹgbẹ̀rún méjìlélógójì (42,000).Èdè èdè abínibí àwọn ẹ̀yà bíShari ní èdè Beja..
wikipedia
yo
Awon Beja ti o tun n gbe ni orile ede Sudan n so ede Sudanese Arabic.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Agbara to waye ni Naijiria ti ọdun 2022 kan ọpọlọpọ awọn agbegbe ni orilẹ-ede naa..
wikipedia
yo
Láti inú déta ti ìjọba àpapọ̀, agbára náà ti sọ eniyan tó ń lọ bíi 1.4 million di àìnínílélórí, ó ti pa eniyan 603, ó ṣe eniyan 2400 léṣe..
wikipedia
yo
Àwọn ilé tó wọ̀ ń lo bíi 82,035, àwọn ilé tó ń lo bíi 332,327 ló sì ti bàjẹ́.Bí ó ti lè jẹ́ pé agbára máa ń wáyé dáadáa ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, àmọ́ agbára ọdún yìí ló léwu jù lọ, láti ìgbà tí èyí tó ṣẹlẹ̀ ní ọdún 2012 wáyé..
wikipedia
yo
Ní oṣù kẹwàá, àwọn ilẹ̀ tó ń lọ bíi 200,000 ni agbára yìí bàjẹ́..
wikipedia
yo
Ní ọjọ́ keje oṣù kẹwàá, ọkọ̀-ojú-omi kan tó ń gbé àwọn ènìyàn tó ń sá àsálà fún ẹ̀mí wọn lọ dojúdé, tíH ó sì fa ikú ènìyàn 76, ìyẹn mẹ́rìnlélọ́gọ́rin.Ohun tó fa agbára náà ni ọjọ́ wẹliwẹli kan tó pọ̀, ìyípadà tó dé bá afẹ́fẹ́, àti omi tó ṣí sílẹ̀ ní làgodo dam ní Cameroon, èyí tó bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹsàn-án..
wikipedia
yo
Agbara naa ṣàkóbá si orilẹ-ede Naijiria, Niger, Chad ati awọn agbegbe rẹ, ti o bẹrẹ ni igba oorun ni ọdun 2022, ti o si pari ni oṣu kẹwàá.agbara naa ni agbegbe to ti ṣẹlẹIpinle adáwa ni ipari oṣu kejo, opo agbara ni Ipinle Adamawa fa iku eniyan mewaa, o si da ọpọlọpọ idile ru.Ìpínlẹ̀ Anambra ni ojo keje oṣu kẹ́wàá, ọdun 2022, eniyan 76 lọ si sinu omi leyin ti ọkọ-oju-omi dojúdé sinu odo.Arin ọdọ Niger ati opo ojo to ro lo je ki omi yẹn kun ni àkúnku..
wikipedia
yo
Àwọn ìlú tó wà ní agbègbè omi ní agbára bàjẹ́.ilé-ìjọsìn alájà mẹ́ta, ìyẹn MaDonna Catostolic Churn ní íyíòwa dà wó látàrí agbára náà, tó wáyé ní ọjọ́ kẹsàn-án oṣù kẹwàá.Àwọn ibùdó idp 28 wà ní ìpínlẹ̀ Anambra, níbití àwọn olùfaragbá ìṣàn omi ti wà ní ààbò àti ti ìtọ́jú lakoko àwọn àkókò pàjáwìrì ìṣàn-omi..
wikipedia
yo
Àwọn ẹlẹ́wọ̀n tó wà ní àgọ́ náà jẹ́ nǹkan bí ẹgbẹ̀rún kan ó lé ọgọ́rùn-ún [1,800]
wikipedia
yo
Àwọn aláboyún marun-un bí ọmọ wọn ní ibùdó ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ Crowther Memorial, Onitsha..
wikipedia
yo
Bí ó ti wù kí ó rí, ìkún omi dé tí ó sì rí olú iléeṣẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ náà nígbà tí àwọn ẹlẹ́wọ̀n wà níbẹ̀..
wikipedia
yo
Àwọn ènìyàn wà ní àyíká pẹ̀lú àwọn ọkọ̀ ojú omi àti gbé àwọn olùfaragbá ìṣàn omi tí ó ní ìdẹ̀kùn kúrò..
wikipedia
yo
Idp ibùdó Umueri idp ibùdó Agulẹ́rìílẹ jìgáwa agbára náà ti kọlu ìpínlè Jigawa láti oṣù kẹjo sí Oṣù Kẹ̀sán-an, nibi ti àwọn ènìyàn bíi méjìléláàádọ́rùn-ún (92) ti ku.Ìpínlẹ̀ Kano ní ìbẹ̀rẹ̀ ọdún, Nigerian Ṣótes Agency fún àwọn ènìyàn ní ìkìlọ̀ nípa agbára omi tó máa ṣẹlẹ̀ ní ìpínlẹ̀ náà.Ìpínlẹ̀ kogi lókọja, tí ó wà ní ibi ìpàdé àwọn odò Benue àti Niger, wà láàrin àwọn agbègbè tí ó ní ipa tí ó burú jù látàrí iṣan omi.Ìpínlẹ̀ Niger ní Mariga, ìpínlè Niger, òkú tí omi ṣàn lọ kúrò nibi òkú òkú ju 1,500 lọ..
wikipedia
yo
Awon osise ijoba so pe oku 650 ni won ri pada, ti won si pada sin.Ipinle Yobe agbara omi nla waye ni Ipinle Yobe ni osu keje ti o si pa eniyan merin.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Àwọn apìtàn gbàgbọ́ pé Matriarch tín Hinan ni ó dá ẹ̀yà náà kalẹ̀, ibojì rẹ̀ wà ní Àbálessa..
wikipedia
yo
Ẹ̀yà náà ní agbára lọ́wọ́ ara wọn, kí ó tó di ọdún 1977, nígbà tí ìjọba Algeria gba agbára lọ́wọ́ wọn..
wikipedia
yo
Àwọn ènìyàn múcuBal (tí a tún mọ̀ sì Mucuiju, Muẹbọle tabi Mugubalẹ) jẹ́ ara àwọn ènìyàn Herero ní apá gúúsù Angola..
wikipedia
yo
Bí àwọn Masai tí wọ́n bá tán, iṣẹ́ dídá màlúù àti iṣẹ́ àgbẹ̀ ni wọ́n ń ṣe..
wikipedia
yo
Ilé wọn wà ní aṣálẹ Namib, Òkè Ser Dá Chela sì ni ó wà ní àríwá wọ́n ti Odò Cunene sì wà ní gúúsù wọn.Àwọn ènìyàn Mherbal kìí wọṣọ púpọ̀, wọ́n sì ma ń mú àdá tàbí ọkọ́ dání lọ ibi tí wọ́n bá ń lọ..
wikipedia
yo
Àwọn ènìyàn mọ àwọn ọ̀kànlélbal fún èmi tí wọ́n ní, wọ́n lè sá eré tí ó tó ní ọjọ́ kan.Ní àwọn ọdún 1930s, àwọn Portuguese sọ pé wọ́n pọ̀ tó ẹgbẹ̀rún márùn-ún, wọ́n sì gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ilé Portugal..
wikipedia
yo
Laarin odun 1939 si 1943, awon omo ologun Portuguese bere si n doju ija ko awon pelusun afisun pe won je ọlọtẹ̀ awon ole màálù, ija naa pa to ara Y-Bal ogorun-un.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Portuguese Angola jẹ́ ọ Angola nígbà tí wọ́n wà lábẹ́ ìjọba Portuguese ní gúúsù ìwọ̀ oòrùn Afrika..
wikipedia
yo
Oruko ko re titi di odun 1951 ni Portuguese West Africa (Tabi State of West Africa).Ní Sẹ́ńtúrì Ògùn ní ìjàdù fún Afrika ni àwọn alágbára ní Europe tó kó gbogbo ìlú náà lẹ́rú.Ìtàn Portuguese jọba lórí Angola láàrin ìgbà tí diògo cao jọba ní ọdún condensation títí ti Oṣù Kọkànlá ọdún 1975..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ nkan ni ó ṣẹlẹ̀ láàrín ọgọ́rùn-ún márùn-ún ọdún yìí.Ìgbà tí wọ́n kó wọn lẹ́rú Angola ó ti sí nígbà tí diògo cao àti àwọn tó kù rẹ̀ dé ìjọba Kóńgò ní àwàtúrì kẹẹ̀dógún..
wikipedia
yo
Ibi tí Angola wà lọ́wọ́ lọ́wọ́ jẹ́ ibi tí oríṣiríṣi àwọn ẹ̀yà àti ènìyàn wà nígbà náà..
wikipedia
yo
Wọ́n sì ní ìbáṣepọ̀ tó dá pẹ̀lú àwọn adarí àti ọ̀tọ̀kùlú ìjọba Kóńgò, wọ́n fi ẹ̀sìn Kristẹni lọ̀ wọ́n, wọ́n sì kọ́ wọn ní èdè Portuguese, wọ́n tún jẹ́ kí wọ́n jẹ àwọn ànfàní oko òwò ẹrú tí wọ́n ń ṣe.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Òfin ti o n Dáàbò Bo Ẹ̀tọ́ Awọn Eniyan ni Somaliland wà ni ori kinni, ẹsẹ kẹta iwe ofin wọn Somaliland..
wikipedia
yo
Somaliland jẹ́ Ìpínlẹ̀ Olómìnira ní Ihò Áfríkà, Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn Àjọ Àgbáyé kà wọ́n gẹ́gẹ́ bi ara orílẹ̀ èdè Somalia..
wikipedia
yo
Amnesty International ti sọ Lodi lọ́pọ̀lọpọ̀ ìgbà sí dídá ọjọ́ Ikú àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ti ti àwọn ènìyàn mọ ẹ̀wọ̀n tí ó ń ṣẹlẹ̀ ní Somaliland.Ní oṣù kínní ọdún 2007, ìjọba kọ àwọn akọ̀wé àti oníròyìn ìwé ìròyìn Háàtuf kan nítorí pé wọ́n "ba orúkọ ìdílé Ààrẹ jẹ́" nítorí pé wọ́n kọ nípa ìwà jẹ́ gùdù jẹrà wọn nínú ìròyìn..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ìgbà tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọmọ ìlú dá sí ọ̀rọ̀ náà, ìjọba Somaliland fi àwọn oníròyìn náà kalẹ̀ lẹ́yìn ọjọ́ mẹ́fà lé lọ́gọ́rin ní ẹ̀wọ̀n..
wikipedia
yo
Àjọ Centre International des Civilisations Bantu (Fictámù) Àjọ Ìbílẹ̀ tí ó wà ní Libreville, Gabon..
wikipedia
yo
Ìjọba Mbata je oruko ti won n pe ijoba Bantu kan ni ariwa mpemba kasi, ki won to da won po mo ijoba nko ni odun 1375 ce.gege bi arọ́ba, won da ijoba nko kale kale nigba ti Oroko a Journama fe Luqueni Luan, omo nsá-Cu-olóko, Oloye awon eniyan Mbata..
wikipedia
yo
Ìgbéyàwó wọn so ìbáṣepọ̀ àárín mpeta kasi àti àwọn ènìyàn Mbata, ìbáṣepọ̀ yìí ni ó jẹ́ ìpìlẹ̀ dídá ìjọba Kóńgò..
wikipedia
yo
Oríkì a ògog ati Luqueni Luansanze, won ni omo ti o n je Lukẹ́ni lẹ́kọ̀ọ́ níku, oun ni o pada di eni akoko lati di mutinú (ọba)àwọn itọkasi..
wikipedia
yo
Cinithians' je awon ẹya Berber ni ariwa Afrika, ti won gbe nibi ti Algeria wa ni ode oni.ọpọlọpọ aworan ati akọle ni o jẹri si pe won gbe ni ibe..
wikipedia
yo
Ni ẹgbẹ githis, ni guusu Tunisia, won se ere lati ye ijoba Roman ati Memmius paPANtus si..
wikipedia
yo
Awon onitan gbagbo pe Memmi ni adari ẹya Cinithithians, oun si ni eni akoko ninu idile rẹ lati di Senato.Ni egbe ileto awon sìtifis, akọle miran tun wa nipa awọn ẹya Cinithithinira.onítàn Cornelius Tacitus tun sọ nipa wọn pe won je "...orile ede ti ko ni ẹgan rara".Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Ogun Pomoka (Ọjọ́ kẹtàlá Oṣù Kọkànlá ọdún 1896) jẹ́ ìjà tí ó ṣẹlẹ̀ láàrín àwọn ogun Fránsì àti àwọn ọmọ ogun iMàmáte of FUTA Klon, tí àwọn ọmọ ogun Fránsì sì ṣẹ́gun àwọn tí ó kù lára àwọn ọmọ ogun Jllon..
wikipedia
yo
Leyin ija yi, won fi tipátipá da foUta Dogbalon mo ijoba Sègábíàbíà.Ìṣẹ̀lẹ̀ to fa èwe ọdún 1890 Bokar bírò se ọ̀tẹ̀ lodi si ijoba nipa pipa egbon re ti o o si fi awon ti o je osu si ijoba lati..
wikipedia
yo
Èyí fa ìjà fún ìjọba tí ó sì mú kí wọ́n le bọkar bírò fún ìgbà díẹ̀ kí ó tó padà débẹ̀..
wikipedia
yo
Orílẹ̀ èdè Fránsì gbìyànjú láti dá sí ìjà wọn ṣùgbọ́n àwọn jàllon fi ònà ẹ̀rú bá wọn Lo.lúgọ Àsìkò ojo ní ọdún 1896, orílẹ̀ èdè Fránsì rán àwọn ọmọ ogun láti Senegal, Guinea àti ní Sudan, gbogbo wọn si parapọ̀ ní FUTA Kabelon..
wikipedia
yo
Ọwọ́ àwọn ọmọ ológun Fránsì tẹ Timbo ní ọjọ́ kẹta Oṣù Kọkànlá ọdún 1896..
wikipedia
yo
Bokar bírò gbìyànjú láti rọ àwọn olóyè láti ran lọ́wọ́ nínú lòdì sí Fráǹsì ṣùgbọ́n akitiyan rẹ̀ já sí Pàbó.Ní ọjọ́ kẹtàlá Oṣù kọkànlá ọdún 1896, àwọn ọmọ ogun Bokar bírò ja pẹ̀lú àwọn ọmọ ogun Fránsì ní Conkaka..
wikipedia
yo
Àwọn ọmọ ogun Fránsì àti Fulbe(ti arákùnrin rẹ, Umaru bádémba Barry jẹ́ olórí wọn) ..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bí akéwì kan ṣe sọ, Bokar bírò kò sá lójú ogun, ṣùgbọ́n ibon ni wọ́n fi pa.Bokar bírò's son Died with him.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Èdè lyele language (lele) jẹ́ èdè kan tí wọ́n ń sọ ní agbègbè Sanguie ní orílẹ̀ èdè Burkina Faso, àwọn tó ń sọ èdè náà tó ọ̀kẹ́ mẹ́fà àbọ̀ (130,000), orúkọ tí wọ́n ń ṣí ń pe èdè yìí ní lyẹlá, Lela, Gourounsì tàbí Gurunsi..
wikipedia
yo
Wọ́n ń ṣọ́ ní ìlú rẹ̀ó, Kyon, tẹtẹ̀ẹ́do, Dassa, Didy, Gody,R, Kordie, Pouni àti Zbáà..
wikipedia
yo
lyele jẹ́ ọ̀kan lára àwọn èdè òderá.Àwọn lẹ́tà AfaBẹti wọ́n wọ́n ma ń lo àwọn àmì sí ará AfaBẹti lyele láti fi ṣe ìyàtọ̀ láàrin ọ̀rọ̀..
wikipedia
yo
ohun oke ati isalẹ ni ami ṣugbọn ti aarin ko ni.Awọn itọkasilyele..
wikipedia
yo
Tael je ibi ti awon Musulumi Marabout ti ja ogun kan ni FUTA jàllon, nibi ti a mo si Guinea ni aye ode oni, awon ogun Musulumi bori, ogun yi si wa lara idi ti won fi da egbe omo ogun iMamate of FUTA jallon kale.Awon adari meji ni agbegbe naa lo lodi si Marabout, won ko fe yi pada si Islam..
wikipedia
yo
Taòpá wa ní ìlà-òòrùn Tímbọ àti ní etí odò báfinfing..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bí àṣà wọn, àwọn ọmọ ológun Mùsùlùmí ọkàn dín ní ọgọ́rũn(99) ṣẹ́gun àwọn alátakò tí iye wọn pọ̀ tó ìlọ́po mẹ́wàá àwọn ogun Mùsùlùmí, wọ́n sì pa ọ̀pọ̀lọpọ̀ wọn..
wikipedia
yo
Síbẹ̀ síbẹ̀, àwọn ènìyàn ibẹ̀ sì kọ̀ láti yí padà sí Mùsùlùmí, pàápàá jùlọ, àwọn adáràn Fulbe..
wikipedia
yo
Wọ́n bẹ̀rù pé àwọn MaraBouts ma lo ẹ̀sìn yi lati fi jẹ gàba lórí wọn.Àwọn mìíràn gbàgbọ́ pe ìjà naa ti bẹ̀rẹ̀ lati ọdún 1727 AD (12 Ah), nigba ti ogun ddd ṣẹlẹ̀..
wikipedia
yo
Àwọn míràn sọ pé ó ṣẹlẹ̀ ní ọdún 1747 tàbí 1748, lẹ́yìn ìjà púpọ̀ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún.àwọn Ìtọ́kasí Ìtọ́kasí nínú ìwé Ìtọ́kasí lórí ẹ̀rọ ayélujára History of Guineala History..
wikipedia
yo
Opha Pauline Dube tabi Pauline Dube (ti a bii ni odun 1960) jẹ Onimọ-jinlẹ Ayika Botswanan ati ojogbon alabaṣepọ ni sàkáání ti Imọ Ayika ni Ile-ẹkọ giga ti Botswana..
wikipedia
yo
O se akọwe ijabọ akanṣe IPCC lori imurúgba agbaye ti 1.5 °C..
wikipedia
yo
An IPCC Special Report on the impacts of Global Warming of 1.5°C Above Pre-Industrial Least and related global Greenhouse Gas Emipetto pathways, in the Context of strengthening the Global response to the atat of Clímate Change, Sustainable Development, and efforts to eradi Poverty [mas-ama-FM, v.. V..
wikipedia
yo
A linked vulgbilẹ̀ and resilience Framework for Adaptation pathways in rẹ́mọte Disadvand communities..
wikipedia
yo
Current Opinion in Environmental Condarainability, 1 (2), 161-169..
wikipedia
yo
doi.org/10.1016/j.cOṣùst.2009.10.008 fiSchlin, A., G.f..
wikipedia
yo
Loting of working group II to the fourth Assessment Report of the intergovernmental Panel on Climate Change..
wikipedia
yo
Cambridge University Press, Cambridge, 211-272.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Apejọ iyipada oju-ọjọ ti United Nations ti ọdun 2001 waye lati ọjọ kokandinlogbon (29) Oṣu Kẹwàá, si ọjọ kẹwàá Oṣu kọkanla, ọdun 2001, ni Marrakech, Ilu Morocco..
wikipedia
yo
Àpérò naa pẹlu Apejọ ẹlẹ́ẹ̀keje ti Awọn ẹgbẹ (COP7) si United Nations Framework convention on Clímate Change (UNFCCC)..
wikipedia
yo
Àwọn olùdúndún náà parí iṣẹ́ náà lórí ètò iṣẹ́ ti lórúkọ lẹ́kòô, tí wọ́n sì parí púpọ̀ nínú àwọn àlàyé ìṣiṣẹ́ àti ṣètò ìpele fún àwọn orílẹ̀-èdè láti fọwọ́ sí ìlànà Kyoto..
wikipedia
yo
ìpinu àpapọ̀ tí wọ́n ṣe ni a mọ̀ sí Marrakech ACCOrds..
wikipedia
yo
Aṣojú Àjọ ti United States n wòye ọ̀rọ̀ náà, ó sì kọ̀ láti kópa tààrà nínú IdunÀdúrà náà..
wikipedia
yo
Àwọn ẹgbẹ́ mìíràn tẹ̀ síwájú nípa níní ìrètí pé United States máa dá sí ètò náà bó bá yá, àti pé wọ́n máa gbé ìgbésẹ̀ láti fọwọ́ sí ìlànà Kyoto nípasẹ̀ nọ́ḿbà àwọn orílẹ̀-èdè tó nílò láti mú un wá sínú agbára..
wikipedia
yo
déètì apejọ agbaye lori ifowosowopo lati mu idagbasoke wa to je osu kejo si osu Keta-an, odun 2022 ni won sun siwaju lati ri daju wipe ero lati mu ilana Kyoto wa si imuse..
wikipedia
yo
Àpéjọ Àgbáyé Lórí Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ yẹ kó wáyé ní Johannesburg, ní South Africa...
wikipedia
yo
Ibudo agbara oorun Ambatola jẹ ile-iṣẹ agbara oorun 40 MW ni Madagascar..
wikipedia
yo
ní oṣù kẹrin ọdún 2022, ó jẹ́ àsopọ̀ àkójọ àkọ́kọ́, ilé-iṣẹ́ agbára oòrùn tí ó ní owó ní ìkọ̀kọ̀ ní orílẹ̀-èdè náà..
wikipedia
yo
Ile-iṣẹ agbara, eyiti a fun ni aṣẹ ni akoko ni ọdun 2018, ṣe imugboroja lati 20 MW si 40 MW, laarin 2021 ati 2022..
wikipedia
yo
olùtajà ti Agbara ti ipilẹṣẹ ní ilé-iṣẹ́ Agbara Iisọdọtun yii ni Jika, Ile-iṣẹ ohun elo ina Amọna ti Orilẹ-ede..Awọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo