cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Trainor ti ko Albumu orin marun-un lati igba naa, o si ti gba ọpọlọpọ ami eye, okan lara re ni ami-eye Grammy ni odun 2016 fun awon olorin titun ti o dara ju lo.Trainor ti nífẹ̀ẹ́ si orin lati igba ti o wa ni omode; o ko awon orin akositiki meta , Meghan Trainor (ọdún 2009), I'll sing with You, ati Only 17 (odun 2010)..
wikipedia
yo
O bẹrẹ kikọ ati agbejade awọn orin fun awọn akọrin miiran ni ọdun 2013..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2015, Trainor ṣe agbejade Alibòmù Pop ati hip hop rẹ, ti akori rẹ jẹ Title, o jẹ orin akọkọ ni ori Billboard orilẹ-ede Amẹrika nigba ti o jade..
wikipedia
yo
O se agbejade awon orin miiran bi “No” ati “Thank You” (ni ọdun 2016) awon orin mejeeji je okan lara awon orin ti awon eniyan gbo ju ni Amerika nigba naa..
wikipedia
yo
Trainor ṣàgbẹ̀ jade Alibòmù orin kẹta rẹ̀ pẹ̀lú Epic, "Treat myself" (2020), ní ìgbìyànjú rẹ̀ láti tẹ̀lé àwọn àṣà orin tí ó nlọ lọ́wọ́, ó ṣe àgbéjáde Alibòmù orin mìíràn tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ A Very Trainor Christmas..
wikipedia
yo
Trainor ṣe agbejade Alibòmù Karun-un orin rẹ ni ọjọ kokanlelogun Oṣu Kẹwa (21 Oct), ọdun 2022, ọkan ninu awọn orin inu Alibòmù naa “ Made You Look ” jẹ ọkan lara awon orin marun-un ti awon eniyan gbo ju nigba naa ni awọn orilẹ-ede bi UK, Ireland, Australia ati New Zealand.Àwọn Orin Trainor ma n saba da lori obinrin, bi eniyan se ri ara rẹ, ati ifiagbara fun ara ẹni, bótilẹ̀ jẹ pe opo sọ wipe awon orin rẹ n lodi si jija fun eto obinrin..
wikipedia
yo
Trainor ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹyẹ bí ààmì ẹyẹ Grammy kan, Ẹ̀bùn AsCap mẹ́rin, àti àwọn Ẹ̀bùn Orin Billboard Méjì.Àwọn ẹlẹ́bùn Grammyàwọn ènìyàn Alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1993..
wikipedia
yo
Ikọ̀ jẹ́ ohun tí ó máa ń wáyé láti mú ikún àti ìdọ̀tí bíi eruku tàbí èéfín kúrò ní àyà wa..
wikipedia
yo
Ikọ̀ fún ra rẹ kìí ṣe àìsàn ṣùgbọ́n wíwú ikọ́ léraléra lè jẹ́ àmì wípé àìsàn wà lára..
wikipedia
yo
Ikọ̀ jẹ́ ọ̀kan lára nkan tí ènìyàn ò ní agbára lé lórí, kódà bí ènìyàn kò bá fẹ́ wúkọ́, bí ìdọ̀tí tàbí àìtọ́ bá ti wọ ọ̀nà ọ̀fun tàbí ẹ̀dọ̀fóró, ìkọ́ má wáyé láti tìí síta, ènìyàn ò lè dá ikọ̀ dúró ìkọ́ wà lára àwọn ọ̀nà tí ara ń fi dábò bo ara rẹ̀..
wikipedia
yo
Bi ó tilẹ̀ jẹ́ wipé ìkọ́ jẹ nkan ti èniyàn kò lágbára lórí, èniyàn fún ra rẹ̀ lè wúkọ́ lati mú ìkan kúrò ní ọ̀nà ọ̀fun fúnra rẹ̀..
wikipedia
yo
Ọpọlọpọ arun ti o n fa iko ni o maa n lo funra rẹ ni aarin ose meta ti won ko si nilo itoju.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀ ìgbóhùngba sáfẹ́fẹ́ lé jẹ́ ìgúnjú padà sí ìparí àwọn ọdún 1950 nígbàtí Western Region tẹ́lẹ̀ ṣe ifilọlẹ ìfihàn ìfihàn àkọ́kọ́ ti Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ní déédé ọdún 1959 ti sàmì ìbẹ̀rẹ̀ ìgbẹ́sáfẹ́fẹ́ tẹlifísàn ní Nàìjíríà pẹ̀lú Western Nigeria Television gẹ́gẹ́ bi ilé-iṣẹ́ tẹlifíṣàn àkọ́kọ́ tí a ṣètò ní orílẹ̀-èdè náà.Ìtàn pẹ̀lú ète pípèsè ọ̀nà fún àwọn ilé ẹ̀kọ́ ẹkùn ti kọ́ ni òṣìṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ tó péye, Western Region tẹ́lẹ̀ tẹ́lẹ̀ dá ilé iṣẹ́ Western Nigerian Television sílẹ̀..
wikipedia
yo
Ni atẹle awọn ipasẹ̀ ti ijọba agbegbe iwọ oorun, ijọba agbegbe ila oorun ṣeto igbẹsafefe tẹlifíṣàn rẹ pẹlu ipinnu akọkọ ti igbega eto ẹkọ deede laarin aṣẹ rẹ..
wikipedia
yo
Ní báyìí, ètò ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ tí a sọ ni a ṣẹ̀dá ní ọdún 1960.Ní ọdún méjì nìkan lẹ́hìn ìgbésẹ̀ nípasẹ̀ ìjọba agbègbè ìlà oòrùn, ìjọba agbègbè àríwá ṣe ìfilọ́lẹ̀ ètò ìgbésáfẹ́fẹ́ tẹlifísàn rẹ̀ pẹ̀lú ìpinnu láti gbé ètò ẹ̀kọ́ láàrín àṣẹ rẹ̀ ga..
wikipedia
yo
Wọ́n fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ ní ọdún 1962, orúkọ tí a fún ètò tẹlifísàn ní "Radio Television Kaduna"
wikipedia
yo
Ní ìbẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ náà, gbogbo àwọn ètò tẹlifísàn agbègbè mẹ́ta dúró pẹ̀lú àwọn ibi-afẹde wọn ṣùgbọ́n ní ẹ̀yìn àwọn ọdún, ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn ti ṣe ìṣọ̀wọ́ níkẹhìn-in.Riagawòrán sáfẹ́fẹ́ tẹlifísàn ní Nàìjíríà bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ìpilẹ̀ṣẹ̀ ti Alákoso agbègbè ìwọ̀-oòrùn (Western Region) àkọ́kọ́, Olóyè Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ tí ní ọjọ́ kọkàn-lé-lọ́gbọ̀n oṣù kẹwàá, ọdún 1959 ló ṣe ìgbékalẹ̀ ìgbóhùngbawòrán sáfẹ́fẹ́ tẹlifísàn ní ìlú Ìbàdàn, tí ó jẹ́ olú agbègbè náà nígbà náà..
wikipedia
yo
Pẹ̀lú àtagbà ọgọ́rún márùn-ún wáàti kékeré tí a gbé sórí òkè Mapo nígbà náà, àti òmìíràn ní àjọṣepọ̀ pèlú ilé-isé British Media, 'Overseas rediÌbéèrè limited '.A tun ṣẹda ‘Western Nigeria Radiovision Service limited ’ pèlú ojuse lati ṣakoso ìgbóhùngba sáfẹ́fẹ́ rédíò àti tẹlifísàn ní agbègbè àwọn ìwọ̀-oorun..
wikipedia
yo
nígbà náà a dá ilé-iṣẹ́ tẹlifíṣàn náà láti tàn ìsọfúnni kálẹ̀ àti láti fi dá àwọn òǹwòran lárayá.Àwọn ìtọ́ka sí..
wikipedia
yo
Obianuju èkénization , ti awon eniyan mo si miran (a bi ni ọdun 1979), jẹ onimo sayensi omo orile-ede Naijiria ti o n gbe ni Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan..
wikipedia
yo
Òun ni olùdásílẹ̀ àti Ààrẹ "Culture of Life Africa".ìtàn rẹ̀ Akaterina n gbé ní orílẹ̀ èdè Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan Ẹ̀ka ibi tí ó ti ń ṣiṣẹ́ ní ẹ̀ka àwọn tí ó ń wo èko fún àìsàn, kòkòrò àti àwọn nkan míràn..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2016, wọ́n fún ní iṣẹ́ sí Ilé ìwòsàn ní Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ara ìjọ Kátólííkì láti ìpìlẹ̀ ṣẹ̀ṣẹ̀ ayé rẹ̀ nígbà tí ó wà ní Nàìjíríà.Ẹ̀kọ́ rẹ̀obijù lọ ilé-ìwé Federal Government Girls' College ti Owerri, kí ó tó tẹ ẹ̀kọ́ rẹ̀ síwájú ní Yunifásitì ilẹ̀ Nàìjíríà, Nsukka, níbi tí ó ti gba àmì ẹ̀yẹ Bachelor nínú ìmọ̀ Microbiology..
wikipedia
yo
Leyin eyi o lo orile-ede Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan lati gba ami eye master ninu imo Biomedical Science ni Yunifásítì East London.Àwọn itọkasi..
wikipedia
yo
Iròrò Kshi (tí a bí ní ọdún 1984 tàbí 1985) jẹ́ ọmọ Nàìjíríà tí ó ní oyè lọ́pọ̀lọpọ̀ nípa àwọn àdán, ó sì ń kọ nípa àwọn orírírí ẹ̀yà àdán ní Áfríkà..
wikipedia
yo
Ó wà lára àwọn olùdásílẹ̀ Small Mammal conservation Organisation (SMI.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ olóòtú ti Coltra.Ru lọ́wọ́lọ́wọ́, èyí tó jẹ́ ìwé àtẹ̀jáde orí ayélujára tí ó dá lórí àṣà àti iṣẹ́-ọnà..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2005, ó gba àmì-ẹ̀yẹ Andei Bely fún ewì Kíkẹ́..
wikipedia
yo
Láìpẹ́, ó tún gba ẹ̀bùn ti 2017-2018 oníwèé ńlá fún ìtàn àròsọ rẹ̀, tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ In Memory of Memory (Pamyati Tíls)àti .Ìtàn Igbesi rẹ̀ Stepanova tí a bí ní Moscow ní oṣù kẹfà ọjọ́ 9, ọdún 1972, kàwé gboyè ní Maxim Gorky Literature Institute, lọ́dún 1995..
wikipedia
yo
Ó ṣe àtẹ̀jáde àwọn ewì nínú àwọn ìwé-ìròyìn pẹ̀lú èdè Russia..
wikipedia
yo
Àpẹẹrẹ irúfẹ́ ewì bẹ́ẹ̀ ni Zerka, Znamya, kriticheskáyà Massa, àti Novoe Literaturun Oboizniye, àti nínú àwọn ìtàn òwúléwutan bíi Babylon, urbi, àti Ulovago..
wikipedia
yo
Stepanova ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ẹ̀bùn pàtàkì fún ìwé-kíkọ ti ìlú Russia, pẹ̀lú ẹ̀bùn Paster àti ẹ̀bùn Andrei Bely ní ọdún 2005, àti ẹ̀bùn ti ìlú Moscow ní ọdún 2006, 2009, àti 2018..
wikipedia
yo
ní ọdún 2007, Stepanova ṣe ìdásílẹ̀ Ogbuspace.Ru, tó jẹ́ iwe-iroyin orí ayélujára tí ó ṣe ìyàsọ́tọ̀ rẹ̀ fún àṣà àti iṣẹ́-ọnà Russiae..
wikipedia
yo
per Stepanova, ìwé ìròyìn náà "yóò pèsè àwọn olùgbọ́ pẹ̀lú ohun-èlò ìgbàlódé, tó pé, àti èyí tó ṣe é fìtara wò lórí ohun tí ń ṣẹlẹ̀ nínú àṣà Russia àti ní ìta lọ́hù. Ó ṣiṣẹ́ olóòtú-àgbà ní Okògbu. títí di ọdún ọdún 2012, nígbà tí ó yọwọ́ kúrò nínú àtẹ̀jáde náà pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn òṣìṣẹ́ olóòtú rẹ̀ nítorí ìṣòro àìróróójì, láti àwọn ilé-iṣẹ́ àdáni..
wikipedia
yo
Wọ́n ti ṣe ògbufọ̀ àwọn iṣẹ́ Stepanova sí èdè Gẹ̀ẹ́sì, Hebrew, Spain, Italy, German, Finnish, French àti àwọn èdè mìíràn..
wikipedia
yo
Wọ́n tún yàn án gẹ́gẹ́ bíi ọ̀jọ̀gbọ́n àlejò ti Siegfried-únṣeld ní Humboldt Universit ní Berlin fún ọdún 2018 – 2019.Àwọn ìtọ́kasí àwọn ènìyàn alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1972..
wikipedia
yo
Taiwo Olayemi Elufioye, Anaòórùn Francisca Oboh Ikuenbe, Gologist Unalizing in Palynology and ìdàpọ̀mento Charia Oluchi Nwaichi, Environmental Biopha, Oreal-UNESCO Award in 2013Janet Edeme Agricultural Scientist and plant biologiste Oni Duọ̀wọ́ náwó Adeyeye omowe Onímọ̀ Sayẹ́nsì Aroko Momo àsémọ́ Gladys fálù Fálùtho FASIvria Oluchi Nwancycycy Jun ogbadu Oroko Titi Odedin Ogunsola Professor of Medical Microbi and University of Lagos First Female Vice-Chancellor.1] Ju Aroko Kshioma Uche Nigerian Pharma-British Nivel and Professor of PharmacyRita Gfunmilayo Nigerian Physicianpàdé Traka Iye First Nigerian Geotemie Gíwá-Tun Founder of Life Bank Bank Ọlakini Ọladunni Taylor, Nigerian Chemist, 2nd Woman Inducted In the Nigerian Academy of Science (now The National root Crops Research Institute) Sadi K (born 1964), Chemi, Lobwe ADEwe Souse, Bo and Environmental Ni Bond Mite Mipha, Kic Mo Ana, Poliàwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Francisca Oboh-ikúenbe jẹ́ onímọ̀ sáyẹ́ńsì ti ẹ̀ka-ìmọ̀ nípa ayé is a (géology) ọmọ nìyíòrùn ní ìjọba-ìbílẹ̀ ẹ̀san South East local government ti ìpínlẹ̀ ẹ̀dọ̀..
wikipedia
yo
Imọ ẹka-ẹkọ rẹ ni palynology ati láìjáfaramentology, bẹẹ naa o jẹ ojogbon ni ẹka-ẹkọ geosciences and Geological and Petroleum and Engineering, bẹẹ naa o jẹ Igbakeji oga Ẹka-Imo Eko, (associate Dean of Academic Affairs in the College of Engineering and Comvting), ti Yunifasiti Missouri University of Science and Technology.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Wọ́n bí Deborah ẹniló Àjàkáiye ní ìpínlẹ̀ Plateau ní apá àríwá Nàìjíríà ní ọdún 1940 bẹ́ẹ̀ náà ló jẹ́ onímọ̀ nípa físíìsì ilẹ̀-ayé.Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Oun ni obinrin akọkọ to jẹ ojogbọ ninu físíìsì ni ilẹ̀ Afirika..
wikipedia
yo
Iṣe rẹ ninu ìmọ̀jẹmọ́ físíìsì Ile-aye ti ran Orilẹ-ede yii lọwọ ninu ìwakùsà.ibẹrẹpẹpẹ Ile-aye ati Eko..
wikipedia
yo
Àwọn òbí rẹ̀ gbàgbọ́ ninu fifún ọmọ ní ẹ̀kọ́ ìwé, yálà ọkunrin tabi obinrin bẹ́ẹ̀ náà ni wọ́n ń pín iṣẹ́ làá ọmọkunrin ati ọmọbinrin..
wikipedia
yo
Ní ọdún 962 ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú físíìsì ní Fásitì ìlú Ìbàdàn..
wikipedia
yo
O tẹsiwaju ninu ẹkọ rẹ ni University of Birmingham Ilu England..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1970, ó gba Ph.D nínu ìmọ̀jẹmọ́ físíìsì ilé-ayé láti Ahmadu Bello University ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
imo nipa iṣiro gan-an ni o wu u lọ́kàn lati se ṣùgbọ́n ÀjàkáIye sọ pe oun ko nipa físíìsì nitori pe yoo ran orile-ede oun lowo.Owó lo si àpérò awon obinrin to je onimo-ero ati onimo sayensi International Conference of Women survi537 and Scientists to waye ni Cambridge ni odun1967..
wikipedia
yo
Wọ́n ṣe àtẹ̀jáde àwòrán rẹ̀ ní àpérò náà pẹ̀lú àwọn onímọ̀ físíìsì orílẹ̀-èdè ẹ̀bùn Adégbohùngbé, nínú àbájáde The Woman Ṣebíeer lórí Àpérò náà ní Oṣù Keje, Ọdún 1967.Iṣẹ́ ÀjàkáIye jẹ́ obìnrin ọ̀jọ̀gbọ́n àkọ́kọ́ nínú ìmọ̀ Físíìsì ní Ilẹ̀ Áfíríkà ní ọdún 1980..
wikipedia
yo
Ó ti ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí olùkọ́ ní Fásitì Ahmadu Bello àtiUniversity of Jos, òun ni olórí Ẹ̀ka ìmọ̀ sáyẹ́ńsì ìṣẹ̀dá ní báyìí..
wikipedia
yo
isere pẹlu ilo-ohun-igbẹkẹle-se-físíìsì-físíìsì nih wọn lo lati ṣe awari awọn ohun alumọni ati omi-ilẹ ni Naijiria..
wikipedia
yo
Ó ṣe wápé Alágún ti Nàìjíríà pẹ̀lú àwọn akẹ́bìnrin rẹ̀..
wikipedia
yo
lẹ́yìn ìfẹ̀yìntì, ó fi àkókò rẹ̀ ṣe Nigeria-based Charity, CCwa, èyí tó dásílẹ̀ ní ọdún 1991.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Olúwaloni Olamide Gíwá ti ọ̀pọ̀lọpọ̀ mọ̀ sí Tèmie Gíwá-Túbọ̀ (tí a bí ní Oṣù Kejìlá Ọdún 1985) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà mọ́ Amẹ́ríkà tí ó ní ìmọ̀ nípa ètò ìlera, òun ni olùdásílẹ̀ Life Bank(ilé-iṣẹ́ tí wọ́n ń pè ní One percent Project), ilé-iṣẹ́ kan ní Nàìjíríà tí ó ń ṣiṣẹ́ takuntakun láti ri sí ìlò Ojúbò ètò ìfun ní lẹ̀jẹ́ ní Nàìjíríà.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Janet Eedeme je onimo sayensi to ni se pelu ohun ogbin ti orile-ede Naijiria ati onimo ijinle ninu ohun ogbin, ti o sise bi oludari eka (Rural economy and Agriculture at the African Union Commission - Auc/drea), ti o wa ni Addis Ababa, ile Ethiopia..
wikipedia
yo
Auc/drea jẹ́ ẹ̀ka kan laarin ìṣọ̀kan Afirika, ti o ni iduro fun igbega, idagbasoke igberiko alagbero nipasẹ iṣẹ-ogbin ati ilọsiwaju ti aabo ounjẹ ni gbogbo ile Afirika.aye ati ẹkọ rẹ edeme jẹ ọmọ orilẹ-ede Naijiria ti wọn bi, to dagba, to si kẹkọọ ni orilẹ-ede rẹ..
wikipedia
yo
Arabinrin naa gba oye Master of Science ninu Agricultural Recognition, pelu imo nipa ohun ogbin ti o da le lori, Yunifasiti ilu Ibadan fun un ni ami-eye..
wikipedia
yo
Dókítà rẹ̀ nínu ìwé-ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ọgbọ́n orí ni wọ́n fún ní ilé ẹ̀kọ́ gíga ní Fásitì Ìbàdàn, Fásitì ti Texas A&M, ní College Station, Texas, United States àti International Institute for Troónyé Agriculture (Iita), ní Ìbàdàn.Ìrírí rẹ̀ lórí iṣẹ́ iṣẹ́ àti ìwádìí èdèmẹ́ dá lórí ààyè ti ìmọ̀-ọ̀gbìn..
wikipedia
yo
O ṣe iwadii ti (Post Domiàti) ni International LiveStock Research Institute (Ilri), ni Ilu Nairobi, ni ile Kenya..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ ní ilé ẹ̀kọ́ tí ó lọ, Fásitì Ìbàdàn..
wikipedia
yo
Ó tún ti ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí olùgbaninímọ̀ràn sí àwọn àjọ tí ó mọ̀ọ́mọ̀, pẹ̀lú ètò Ìparapọ̀ Àwọn Orílẹ̀-Èdè lórí HIV/AIDS (Joint United Nations programme on HIV/AIDS - UNAIDS) àti Àjọ tó ń bójú tó oúnjẹ àti àgbẹ̀ ti Ìparapọ̀ Àwọn Orílẹ̀-èdè - Food and Agricultural Organisation of the United Nations (FAO).Ohun mìíràn tí a mọ̀ ọ́ fún èdème jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ tí Ìgbìmọ̀ Alakoso ti àwọn Irúgbìn Áfíríkà, Àjọ láàrín Ìjọba, láàrín Ìṣọ̀kan Áfíríkà (African Union), tí ó ní ìdúró fún ìmúṣẹ ètò African Tarato and OcDOU programme.Àwọn Ìka Sí..
wikipedia
yo
Professor ẹbun Oni (ti a bi ni ọjọ 21 Oṣu Karun-un, ọdun 1935 -ti o si di Oloogbe ni ọjọ 2 Oṣu kejila, ọdun 2021) ni a mọ si ẹbun Agbegbohùngbé nigba aye rẹ, ti o wa pada di ẹbun AdefunMilyo oni (orukọ ọkọ rẹ)..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ onímọ̀ sáyẹ́ńsì tó ń fi ohun àfojúrí fi kẹ́kọ̀ọ́ nípa ayé , ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni, ó jẹ́ olùkọ́ ní Yunifásitì àti ònkọ̀wé..
wikipedia
yo
Ó tún jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ Nàìjíríà tó kọ́kọ́ di onímọ̀ ìtayẹ́nsí àkọ́kọ́, ó sì di ìlú-mọ̀-ká-kà látàrí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé àtẹ̀jáde rẹ̀..
wikipedia
yo
Olùkọ́ ní Yunifásítì ìlú Ìbàdàn ni.ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ Adégbóhùngbé jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ ti ilé-ìwé Methodist Girls High School, Yaba, Lagos kí ó tó lọ kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ìmọ̀ physics ní University College of Ghana ní ọdún 1961..
wikipedia
yo
Iṣẹ akọkọ to yan laayo ni iṣẹ imọ-ẹrọ, kódà ni ọdun 1967 o sọ pe oun ni lọkan lati jẹ obinrin akọkọ to maa kọ nipa imọ-ẹrọ, amo ijọba ko jale lati fun oun ni anfaani iwe ọfẹ tori o jẹ obinrin, nitori naa wọn gba a niyanju lati kọ ẹkọ nipa Physi.adelẹgbe gba iwe-ẹkọ ọfẹ ti ijọba fun itẹsiwaju ninu ẹkọ rẹ, ninu Geophysics ni Imperial College, London..
wikipedia
yo
O gboye MSc ni ọdun 1963, ọdun kan naa ni o dara pọ mọ awọn oṣiṣẹ ẹka-ẹkọ Physics ni University of Ife, Naijiria.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Helen noSakharé Abọ́ú jẹ́ Baọ́títẹ́ àti Baidologisiti nípa nǹkan ọ̀gbìn tó wà ní Jamaica..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n fún Baọ́títẹ́ àti mọ́lẹ̀kula bíoloji àti adarí fún Senta bánamiologiss fún Fásitì West Indies ní Mona, Jamaica..
wikipedia
yo
Àwọn ìwádìí rẹ̀ mú ìlọsíwájú bá Baitekìnologisiti nípa bí wọ́n ṣe máa ń ṣe nǹkan àti ìtẹ̀síwájú bá àwọn nǹkan ẹ̀ṣọ́-oko..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tó wà ní iwájú fún ìbáṣepọ̀ báòÀkàràologisiti ní àgbàláàyè, bẹ́ẹ̀ náà ló jẹ́ ẹni tí wọ́n máa ń gba ìmọ̀ràn lọ́wọ́ rẹ̀ ní gbogbo ayé lórí báò?“Kinsiti fún United Nations (un).Ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí Agbiké ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O gba oye ipari ẹkọ rẹ ni Fasiti Benin, o gba oye masitasi lori imo ijinle sayensi ni ​ Ahmadu Bello, ati Dokita ni Filo ni Fasiti/Fasiti Frankfurt iye .Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Adeyinka Gladys Falúsì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìmọ̀ Ẹ̀jẹ̀ àti Omi Ara ní Nàìjíríà, òun sì ni olùdarí tẹ́lẹ̀ rí fún ibi ẹ̀kọ́ "Advanced Medical Research and Training, College of Medicine, ti Yunifásítì ìlú Ìbàdàn..
wikipedia
yo
O ni ìmọ̀ pupọ ninu àwọn àwọn àìsàn ẹ̀jẹ̀ tí ó ń pa eniyan lára.Ìpìlẹ̀ ati ẹ̀kọ́ rẹ Gladys jẹ́ ọmọ bíbí ipinle Ekiti, Naijiria, wọ́n tọ́ dàgbà ní ẹfọ̀n alààyè, ìpínlẹ̀ Ekiti, Naijiria..
wikipedia
yo
Arabinrin kan (Grace Oladunni Olaniyan, ẹni ti o ti di ojogbon Taylor) ti o n gbe ni adugbo Gladys ni o mu ki o ko nipa imo sayensi..
wikipedia
yo
Ó kọ nípa ìmọ̀ Kemistri ní Yunifásítì ìlú Ìbàdàn (UI)..
wikipedia
yo
O tẹ ẹkọ rẹ siwaju lati kọ nipa ẹjẹ ati omi ara ni College of Medicine ti Ibadan.idile rẹ ojogbon Gladys fẹ ojogbon Abiodun faLusi, ojogbon ninu imo Agricultural Economics, won bi omo marun-un.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Ijeoma Uche jẹ ojogbon ti Eko nipa imọ-oogun ni University College London, nibi ti o ti dipo Igbakeji Aare mu fun ile Adulawo ati aarin-gbùngun..
wikipedia
yo
Òun ni Olórí Oníṣẹ́ Sáyẹ́ǹsì ti Nanomerics, èyí ti n ṣe ilé-iṣẹ́ tó n ṣe òògùn lati wá ojútùú si omi ti ó mọ́..
wikipedia
yo
Òun sì ni gómìnà WellCome, èyí tí ń ṣe ilé-iṣẹ́ òògùn tó ń ṣe ìwádìí, tó sì ń fi inú-rere hàn fún àwùjọ..
wikipedia
yo
Rita Oluchi Orji jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí ó tún fi apa kan tàn mọ́ Kánádà..
wikipedia
yo
O jẹ onimo kosíbì fun Kanada ninu iwadii jinlẹ fun egbe paṣúà..
wikipedia
yo
àti olùdarí Paṣúà KoKols Lomibu ti ilé ẹ̀kọ́ gíga Yunifásítì Dalhoúsì..
wikipedia
yo
Iṣe rẹ da le lori bi a se le lo iṣoro n ìtànìgbésí laarin eniyan ati ẹrọ Kọmputa.O ti gba ami ẹyẹ to ti to aadọrin, ati ami idanimọ ni agbegbe, ayika ati agba-n-la-aye..
wikipedia
yo
O si tun ṣe iṣẹ pataki nipa riri si Asia àwọn obìnrin nínú ẹgbẹ Àjọ àwọn Orílẹ̀-èdè Panel, ti Ilé Igbimọ Aṣòfin Kánádà...
wikipedia
yo
Lucy Jumèyí Odu (ti a bi ni ọjọ arun-din-lọgbọn osu Kesan-an ọdun 1953) jẹ onimoran Microbiologist ti orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
O si sise gege bi oludari agba ati alakoso National DoNiger Development Agency (Nabda), Ile-iṣẹ iwadii labẹ Ile-iṣẹ ti Imọ-jinlẹ ati Imọ-ẹrọ ti Naijiria titi di ipari asiko rẹ ni ọdun 2018.Iṣẹ rẹṣaaju ki o to ṣiṣẹ gẹgẹ bi Oludari Gbogbogbo ati Alakoso ti Nabda ni Oṣu kọkanla ọdun 2013, Ọgbadu ti kọ ẹkọ ni ile-ẹkọ giga rẹ ti Ahmadu Bello University, Zaria, fun ogun ọdun ati lẹhin naa ni Fasiti Ipinle Benue, sibẹsibẹ, fun ọdun mẹfa miiran..
wikipedia
yo
ní ọdún 2002 wọ́n yàn-án gẹ́gẹ́ bí olùdarí ìwádìí àti ìdàgbàsókè ní Nabdà àti lẹ́hìn náà ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí olùdarí bíó láti ọdún 2004 sí ọdún 2005..
wikipedia
yo
Ope tun ṣiṣẹ nibi agbara iṣẹ gẹgẹ bi Oludari Gbogbogbo ati Alakoso ti Nabda fun Oṣu Mẹta ni ọdun 2005, lẹhin naa o di olori..
wikipedia
yo
Ti Ẹka Food and Industrial Dokàmàmà ni Nabda lati ọdún 2005 sí ọdún 2011..
wikipedia
yo
O tun sise gege bi oludari iwadii lati 2011 titi di ọdun 2013, nigba ti won yan si ipo rẹ lọwọlọwọ.Awon atẹjade ogbadu ti ṣe atẹjade iwe iroyin ju ogoji lo / iwe ti awon awari iwadii rẹ, ida ẹ̀tà-din-láàdọ́rin ninu eyiti o wa ninu awon iwe iroyin agbaye olokiki ati iyoku ninu awon iwe iroyin agbegbe / awon iwe giga ti o wa ni ipo giga..
wikipedia
yo
Ọgba ti ṣe alabapin awọn ipin si elsevier encyclopedia of food Microbiology..
wikipedia
yo
O ti ṣafihan lori ṣemina eji-le-logun ati awọn iwe apejọ ni ọpọlọpọ awọn apejọ imọ-jinlẹ.awọn itọka si..
wikipedia
yo
Grace Oladunni Taylor (ti a tun mọ si Grace Oladunni Lucía Olaniyan-Taylor; ti a bi ni ojo 24 Osu kerin, odun 1937) je BioNOst, ni Yunifasiti ilu Ibadan nigba kan ri..
wikipedia
yo
Oun ni obinrin eleekeji ti won maa gba wole si Nigerian Academy of Science ati obinrin ile Adulawo akoko lati gba ami-eye l'Ore-UNESCO Award for Women in Science.ibẹrẹ ati eto-ẹkọ re ilu Efon-aláìyẹ, ni Ipinle Ekiti,ni a bi Grace Oladunni Lucía Olaniyan si, sinu idile Elizabeth (née OlaToun) ati R..
wikipedia
yo
Láàárín ọdun 1952 ati 1956, ó jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ ilé-ìwé Queen's School ní ẹ̀dẹ ní ìpínlẹ̀ Osun.O forúkọ wọlé sí ilé-ìwé gíga ní ọdún 1957 ní Nigerian College of Arts and Science ní ìpínlẹ̀ Enugu, ní ọdún 1959, wọ́n gbé lọ sí Yunifásítì College of Ibadan (tí ó wà di Yunifásitì ìlú Ìbàdàn báyìí)..
wikipedia
yo
Olaniyan kẹkọọ gboye pẹlu esi to da ni ọdun 1962, pẹlu iwe-ẹri ninu Eko Chemistry.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
sádik (tí a bí ní ọjọ́ 19 osù kẹfà, odún 1964) jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, onímọ̀ nípa òògùn, àti aṣẹ̀dásílẹ̀ ohun ọ̀tun tó ń ṣiṣẹ́ ni Binghamton University..
wikipedia
yo
O ti ṣàgbékalẹ̀ Microelect| biose-konrs fún Ṣíṣàwárí oògùn àti èròjà bombu..
wikipedia
yo
Ó sì ń ṣiṣẹ́ lórí ìdàgbàsókè àwọn ẹ̀rọ amáyérọrùn fún ìlòtunlo èròjà irin láti inú ìdọ̀tì, fún lílò láwùjọ..
wikipedia
yo