cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ó se ojú orílẹ̀-èdè rẹ̀ ní ìdíje 2016 Summer Olympics ní 50 mítà eléré ó gbé ipò 77th pẹ̀lú àsìkò 27.32 ìṣẹ́jú àáyá..
wikipedia
yo
Ko yanjun si ipele ti o kangun si asekagba.Sanbes si ni eniti ami eye orile-ede Benin ninu 50 mita elere ati 50 mita Oyan.Awon itọkasi awon eniyan Alààyèawon Ọjọ́ìbí ni 1979..
wikipedia
yo
Alois ÈmiÈmi (ojoibi 1982) jẹ olówe Olimpiiki lati Ilu Benin ..
wikipedia
yo
Christophe Pognon (ti a bi ni ọjọ kankanla Oṣu Kẹwa Ọdun 1977, ni Cotonou ) jẹ oṣere tẹnisi tẹlẹ lati Benin .non ṣe aṣoju orilẹ-ede abinibi rẹ ni Olimpiiki Igba otutu 2000 ni Sydney, Australia, nibiti o ti ṣẹgun ni ipele akọkọ nipasẹ Gustavo Kucasal Brazil ..
wikipedia
yo
Eni ti o ni owo ọtun de ami iyasọtọ ATP ti o ga julọ ni ipo ni ọjọ 27 Oṣu Kẹjọ ọdun 2001, nigbati o di nọmba 804 ni agbaye..
wikipedia
yo
Pognon ṣe alabapin ninu ìdíje Davis Cup fun orilẹ-ede Benin lati 1994–2003, ti o fi Ami 14–17 kan silẹ niti ẹlẹ́yọkan ati itan 1–1 ni eleeyanmeji.Ita ìjápọ Christophe Pognon at the International Tennis Federation Awọn Ọjọ́ìbí ni 1977àwọn ẹ̀nìyàn Alààyè..
wikipedia
yo
Aloys Nizigama (ti a bi ni ojo kejidinlogun osu Okudu odun 1966) jẹ asare olona jinjin ọmọ ilu orile-ede Burundi ti o ti fẹhinti ti o ise re je ti mita 5000 ati 10,000 .ninu ise re, Nizigama sa ere-ije ni iṣẹju 21 ati iṣẹju-aaya-28 ni 10,000 mita , ni ipo keji si Haile GbrSelassie pelu akoko 23.idije okeere awon eniyan awon eni Ọjọ́ìbí ni 1966..
wikipedia
yo
Konlátì Omorẹ́gíe, ti a mọ mọ́ ìṣe rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí i Nosa, jẹ oníṣẹ́-Onriaria, olórin, A-kọ-orin àti elere..
wikipedia
yo
Ó wà lábẹ́ Warner Music Group African partner lọ́wọ́lọ́wọ́, chocolate City.ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ Ìgbé-ayé Nosa Omorẹ́gíe, tí wọ́n mọ̀ ní ṣókí gẹ́gẹ́ bí i Nosa, ni wọ́n bí ní 26 Oṣù Kejì ọdún 1981, ó jẹ́ ọmọ ìlú Benin City, ìpínlẹ̀ Edo.Èkó ó kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìmọ̀ ẹ̀rọ ní Yunifásítì Benin (Uníbẹ̀n)..
wikipedia
yo
Ìpínlẹ̀ ẸdóỌ́dọ́ Àìbí Ayọ̀ Nosa gẹ́gẹ́ bí ọmọ tí ó ń dàgbà wà nínú orin àti lílọ sí ilé ìjọsìn, níbi tí ó ti bẹ̀rẹ̀ sí ṣe àmúlò àwọn ẹ̀bùn rẹ̀ ti ń gbèrú..
wikipedia
yo
O bẹrẹ ninu ẹgbẹ akọrin ọmọde ni ile ijosin, awon olorin emi bi i Fred Hammond ati Kim Burrell si ni won je esin iwaju ti o n wo sare ati awon ẹgbẹ olorin r n b Boy II Men..
wikipedia
yo
O ní láti nífẹ̀ẹ́ orin Jazz àti orin Soul àti lẹ́yìn náà orin Rock nígbà tí ó yá, fún rírọrùn tí ó rọrùn..
wikipedia
yo
.Won se agbejade awo orin rẹ akọkọ, Open doors, ni 14 Oṣu Kẹta 2014 o si se atilẹyin rẹ pẹlu awọn Eyo Orin "Always pray for You", "Why You Love Me" ati "Always on My Mind"
wikipedia
yo
ati bakan naa ni Oṣu Karun-un 2014, o pawọ́pọ̀ pẹlu nokia fun agbejade orin rẹ “Love iṣ calling”
wikipedia
yo
Ní ọjọ́ 16 oṣù karùn-ún 2014, ìwé ìròyìn The Punch sọ pé Nosa tọwọ́bọ̀wé àdéhùn iṣẹ́ ìpolówó pẹ̀lú Unilever..
wikipedia
yo
Ní ọjọ́ 26, Oṣù Kejì 2020, tí ó tún jẹ́ ọjọ́ ìbí rẹ̀, Nosa bẹ̀rẹ̀ ilé-iṣẹ́ orin rẹ̀ Salt Music.Iṣẹ́ orin àti orin-ẹyọ tí ó gbé e jáde Nosa lọ sí abẹ́ ilé-iṣẹ́ orin Chocolate City ní 2012..
wikipedia
yo
Ní 11 Oṣù kọkànlá 2009 Nosa ṣe àgbéjáde orin-ẹyọ rẹ̀ àkọ́kọ́, "Always pray for You", labẹ Ile-iṣẹ Chocolate City..
wikipedia
yo
"Always pray for You" jẹ ẹyọ-orin Nosa akọkọ .Àtòjọ orin Reawo Open doors (2013)orin-ẹyọ..
wikipedia
yo
Mary Kínùsóde jẹ́ agbábọ́ọ̀lù lobinrin ilé Kenya tí a bini 19, oṣù February ní ọdún 1990..
wikipedia
yo
Arabinrin naa ṣere gẹgẹbi Fordaradayori kopa ninu Nations Cup awọn obinrin ile afiricaitọ́kasí..
wikipedia
yo
Annette Kunku je agbaboolu lobinrin Ile Kenya ti a bini 17, Oṣu December ni ọdun 1996..
wikipedia
yo
Agbáré náà ṣòbá gegebi Gotà8.Annette kópa nínú Nations Cup àwọn obìnrin ilé afíko to wáyé ní ọdún 2022.itọkasi..
wikipedia
yo
Sylvia Lumásíà jẹ́ agbábọ́ọ̀lù lobinrin ilẹ̀ Kẹ́nyà tí ó ṣeré fún ilé ẹ̀kọ́ lórí bọ́ọ̀lù ọ̀dọ́mọbìnrin kíwọ́n gẹ́gẹ́bí Fordayọrisylvia kópa nínu eré ìdíje Olympic tó wáyé ní ọdún 2020.Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Enez mango jẹ agbabọọlu lobinrin ile Kenya ti a bini ọjọ akọkọ, oṣu July ni ọdun 1993..
wikipedia
yo
Agba naa ṣere fun Vihiga Queens FC gẹgẹbi Left wing Backasee-e jẹ Captain fun Vihiga Queens FC ati team apapo awon obinrin lori bọ́ọ̀lù.Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Rachael Mumaẹ jẹ agbabọọlu lobinrin Ile Kenya ti a bini 6, Oṣu October ni ọdun 1999..
wikipedia
yo
Agbaji naa ṣere gẹgẹbi midfielder fun Thika Queens FCaṣeyọriRachael kopa ninu Cup awọn obinrin ile Turkey ti ọdun 2020 nibi ti o ti ṣoju team National awon obinrin lori bọ́ọ̀lù.Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Doreen Navwire je agbaboolu lobinrin orile ede Kenya ti a bini 5, osu March ni odun 1987..
wikipedia
yo
Arabinrin naa ṣere fun Masar Zwolle FC gẹgẹbi midfielder.aṣeyọrita je obinrin akọkọ ile Kenya lati ṣere bọọlu ni ile Europe..
wikipedia
yo
Arabinrin naa tun jẹ director awon obinrin agbaboolu fun Federation boolu Ilu Kenyaitọkasi..
wikipedia
yo
Christine NAUF jẹ́ agbábọ́ọ̀lù lobinrin ilẹ̀ Kẹ́nyà tí a Bìní 10, Oṣù November ní ọdún 1991..
wikipedia
yo
Agbágbá náà ṣòbá gegebi midfiàṣeyọrí. kópa nínú Nations Cup àwọn obìnrin ilé afi To wáyé ní ọdún 2016. yìí.
wikipedia
yo
Vivian NASAka jẹ́ agbábọ́ọ̀lù lobìnrin orílẹ̀ èdè Kẹ́ńyà tí a bini 19, oṣù December ní ọdún 1999..
wikipedia
yo
Arabinrin naa ṣere gẹgẹbi Defender fun Vihiga Queens FC.aṣeyọrikunkun kopa ninu ere idije Wakatif Awọn obinrin to waye ni ọdun 2019.itọkasi..
wikipedia
yo
ADEADE Àkànjí (ibi 1930) jẹ́ òṣèré ti orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, bákan náà ó sì jẹ́ Olóyè Olúwo Nini ilé Yàrá ilédì karùn ohuntótó, èyí tí ó jẹ́ Oní tí ó jẹ́ gbòógì ti ìbílẹ̀ ti ti Ìlú Òṣogbo, ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ayé àti ìwé kíkà ni gba tí ó gbọ́njú, ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí àmíràn bíríkì Bridu, lẹ́yìn èyí, ó bẹ̀rẹ̀ sí ní gbe ère lati lè gbáradì fún ìdíje èyí tí ó sì gbé àwọn ẹranko tí ó dúró fún àṣà èyí tí ó wà fún ohun ọ̀ṣọ́ fún inú ilé ( agbo èlégiiments). Dúró jẹ́ ẹnití ó gbajúmọ̀ fún iṣẹ́ àgbẹ̀dẹ àti àwọn iṣẹ́ eré..
wikipedia
yo
Ó sì tún ti ṣiṣẹ́ ní ilé iṣẹ́ aṣọ àwọn iṣẹ́ rẹ̀ a máa ṣàlàyé àwọn ìsọ̀rí àlọ́ ilẹ̀ Yorùbá [Yorùbá People|Yorùbá]]
wikipedia
yo
Ni ibaṣepọ pẹlu Susanne Wenger, o ti sise fun odun mewaa ni ojúbọ Osun ni ilu [Òṣogbo] ni orile ede Naijiria, oun yii naa lo gbe awon ere miiran ni Ibeàwọn.Awon itọkasiExternal State–Century Nigerian Nigerian Uxtors Artists1930s Births Eniyan Alààyèlo Brickrs Nigerian Artists (21st-Century Uxtors Uxptors of Birth Missing (Living People)Yorùbá People..
wikipedia
yo
Lorna Nyarinda jẹ agbabọọlu lobinrin orile ede Kenya ti a bini 13, oṣu October ni ọdun 2000..
wikipedia
yo
Agba naa ṣere gẹgẹbi midfielder fun Vihiga Queens FC.aṣeyọrir-na ṣe debut fun awọn agbagbo to Oriku fun Nation Cup awọn obinrin ile afitun ni ọdun 2022.itọkasi..
wikipedia
yo
Sunday Jack Akpan (oruko ibiso re ni IKOT Idẹ Etudo, 1940) je gigi kere ti orile ede Naijiria ti won n pe ni ede Geesi ni "The Contemporary African equxnt of the medieval artisan arti..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ gbajúmọ̀ fún iṣẹ́ rẹ̀, iṣẹ́ eré èyí tí ó máa ń lo Simeti Cece, èyí tí ó máa ń fi ń gbé àwọn ère ìbílẹ̀ fún àwọn ẹni oyè àti àwọn èèyàn Janjàkàn, àti àwọn ojú ìbojú grave art, lẹ́yìn náà ni yóò wá kun ọ̀dà; ó ti ṣe àwọn iṣẹ́ eré lóríṣìíríri, èyí tí ó wà fún títa Commercial Arts, àwọn bí àlùfáà ìjọsìn àti àwọn èèyàn Jankande ní àwùjọ..
wikipedia
yo
Awon ise Èrèlé re wà ní ìfihàn ní Venice binna ati ní gbàgede Centre Popààlàpààlàdou ni Paris, ati àwọn gbàgede ìfihàn mìíràn..
wikipedia
yo
àwọn ìṣe rẹ̀ náà ní Horniman Museum ní London.Àwọn ìtọ́kasíàwọn Ọjọ́ìbí ní 1940àwọn ènìyàn Alààyè20th-Century Nigerian Uxv-Century Ux-Century-Century Nigerian Malelé-Ma lọdọ Nigerian male Artists..
wikipedia
yo
Jacky Iogo jẹ agbábọ́ọ̀lù lobinrin orílẹ̀ ède Kenya tí a bí ọjọ́ kejì, Oṣù December ní ọdún 1994..
wikipedia
yo
Arabinrin naa ṣere gẹgẹbi midfielder.aṣeyọriation kopa ninu ere idije Jimọfa awọn obìnrinítosóko..
wikipedia
yo
Emmanuel Taiwo Jẹ́gẹ́dẹ́ (ti a bi ni June 1943) je akewi omo orilẹede Naijiria, Akowe itan, Oluyaworan, àtèwe ati alaworan (ninu igi, Idẹ ati Ṣéràmi).Ìbéèrè aye rẹ ati Eko Emmanuel Taiwo je omo bibi ilu Ayegbaju Ekiti, a Yoruba-Speaking agbegbe ti Naijiria.O ko ise ere mimo lati owo pa akéréjọlá ni Ekiti leyin ti o lo si Yaba School of Technology in Lagos, nibi ti o ti ko nipa Edo Uxptor2gíẹ́ osifo osifo.Ni odun 1963 o rin irin ajo lo si oke on ti o ti o ti kawe Willes College of Technology of Technology Hammersmith College of Arts, studying the rative, Enugu arts, 17 kọja and Brond sting...
wikipedia
yo
1938) Ni èrò àwọn òpìtàn iṣẹ́-ọnà ti wọn jẹ òyìnbó àti àwọn olùgbàsílẹ iṣẹ́-ọnà jẹ ọkan ninu awọn ti o ṣe pataki ju ni sétúrì 20 láàárín àwọn oníṣẹ́-ọnà ti àwọn ara Yorùbá ti o jẹ Naijiria oni, Afirika ..
wikipedia
yo
ó jẹ́ agbẹ́gilére igi a-gbẹ́-ère àti ọ̀gá olùdásílẹ̀ nínú ara iṣélélọ́ṣọ̀ọ́ Áfíríkà tí a mọ̀ sí ojú-ọ̀nà.Olóyè, ti wọ́n mọ́ láti ilẹ̀ sí ọlọ́wéré, ni wọ́n bí ni ẹ̀fọn-aláìyẹ, ìlú kan ti wọ́n mọ̀ gẹ́gẹ́ bí ọ̀gangan ibi àṣà ni ilẹ̀ Yorùbá, ṣùgbọ́n ó gbé púpọ̀ àyè rẹ̀ ní ìgboro iṣẹ́..
wikipedia
yo
Wọ́n gbà á láti ìbẹ̀rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìránṣẹ́ ní ààfin ọba Anajalè, ọba ti íṣe..
wikipedia
yo
ó jẹ́ ọ̀rọ̀ àríyànjiyàn bóyá iṣẹ́ iṣẹ́-ọnà rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí i ọmọ ìkọ̀sẹ̀ tàbí ó dìde tààrà láti ẹ̀bùn rẹ̀ lásán..
wikipedia
yo
Òkìkí rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi i agbẹ́gilére hàn láti bẹ̀rẹ̀ ní iṣẹ́ lábẹ́ àtìlẹ́yìn àrinjalè ṣáájú kí ó tó tàn ká apá ìlà-oòrùn ilẹ̀ Yorùbá..
wikipedia
yo
Wọ́n pe olówe lọ sí Iléṣà, Ikẹrẹ, Àkúrẹ́, Ìdanrẹ̀, Ogi àti àwọn ìlú Yorùbá mìíràn tí ó wà ní ààrin máìlì ọgọ́ta (96.75 Ọlákún) láti ṣe àwọn ohun èlò ilé ńlá (gẹ́gẹ́ bí i àṣẹ àti àgaran ) , ohun èlò ara àti ètùtù fún àwọn ìdílé olówó.Ipò iyì olówe gẹ́gẹ́ bí i oníṣẹ́-ọnà jẹ́ gbígbàsílẹ̀ láti ọwọ́ àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ nínú ewì alohùn Yorùbá tí a mọ̀ sí oríkì..
wikipedia
yo
Fún àpẹẹrẹ , èyí example ti ọ̀kan lára àwọn ìyàwó rẹ̀ kọ̀ tí wọ́n gbasílẹ̀ ní 1988.Òkìkí Òkè-Òkun ní 1924, wọ́n ṣe àfihàn iṣẹ́-ọnà olówe ní òkè-òkun fún ìgbà àkọ́kọ́ nígbà tí wọ́n yan àṣẹ olókè láti ààfin ọba ní Ikẹrẹ fún pafili Nàìjíríà ní British Empire Exhibition ní Webley, London..
wikipedia
yo
Felix ìdùbúbor (1928-1991) jẹ́ agbẹ́gilére Nàìjíríà láti ìlú Benin, ìlú kan tí ó ní ìtàn tí ó lọ́ọ̀rìn nípa ìmọ̀óṣe iṣẹ́-ọnà..
wikipedia
yo
O jẹ ọkan lara awọn ẹgbẹ kekere awọn oniṣẹ-ọna ni aarin 1950 ati 1960 ti wọn ṣe igbende ìdálẹ́kọ̀ọ́ mimọ nipa iṣẹ-ọna iṣẹ Afirika ni dide ati ni ibẹrẹ ọwọ eniyan ayika..
wikipedia
yo
Wọ́n máa ń gbé e wọ̀ ní àwọn ìgbà kọ̀ọ̀kan gẹ́gẹ́ bí i ọ̀kan lára àwọn olùdásílẹ̀ iṣẹ́-ọnà ìgbàlódé Nàìjíríà ..
wikipedia
yo
Ni 1966, o si ile-iṣafihan iṣẹ-ọna igbalode akọkọ ni Naijiria si opopona kakawa, Eko.O yege gan-an ninu gbigbe aṣẹ, o si ni aṣẹ lati maa gbe aṣẹ fun awọn ile-iṣẹ nlanla ati awọn eniyan bi apẹẹrẹ ile ile-ifowopamọ Cooperative ni Ibadan ati ile igbimọ aṣofin ni Eko.ibẹrẹ igbesi-aye ati ẹkọ wọn bi Felix ìdùbúbor sinu idile agbe ni Ilu Benin..
wikipedia
yo
Ó bẹ̀rẹ̀ sí gbẹ́níjì ni àti kékeré, ṣùgbọ́n ó rí àwọn àtakò kan láti ọ̀dọ̀ baba rẹ̀ tí ó lérò pé gbígbé ilé rẹ̀ kì í ṣe iṣẹ́ tí í mówó wọlé..
wikipedia
yo
O bẹrẹ ẹkọ rẹ ni ile-iwe alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ni Benin ṣùgbọ́n ó gba ìsinmi nínu ìwé kíkà nígbà Toya láti lè gbájúmọ́ ohun tí ó rò pé ó jẹ́ iṣẹ́ Àmọ́ rẹ̀, gbígbég.[re..
wikipedia
yo
Àrírí iṣẹ́-ọnà rẹ̀ àkọ́kọ́ tí ó yàn dáọdún àwọn ẹ̀yẹ tí wọ́n gbé ní ọ̀pọ̀ ìgbà láti ara Ìrókò igi tí ó pọ̀ ní Benin..
wikipedia
yo
Ó tún lo àwọn igi láti ara ìrókò gẹ́gẹ́ bí i ohun èlò iṣẹ́ ní àwọn iṣẹ́ gbígbẹ́kùn ó sì yege nínú ọ̀nà tí ó yàn..
wikipedia
yo
Nígbà tí yóò fi pé ẹni ọdún ẹ̀tàdínlógún, wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bí olùkọ́ni ní ẹ̀dọ College ní Benin pẹ̀lú ìwọnba ìdánilẹ́kọ̀ọ́ àìgbẹ́..Ni òpin àárín 1950, ó jẹ́ ẹ̀bùn ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ láti kẹ́kọ̀ọ́ ní Royal College of Art, London lẹ́yìn tí iṣẹ́ rẹ̀ gba ìyìn pàtàkì nígbà ìṣmoṣe kan tí ó wáyé papọ̀ pẹ̀lú ìrìn àjò Queen Elizabeth's sí Nàìjíríà...
wikipedia
yo
Irene Ogutu jẹ́ agbábọ́ọ̀lù lobinrin orílẹ̀ ède Kenya tí a Bìní 14, Oṣù June ní ọdún 1987..
wikipedia
yo
Agbágbá náà ṣòu gegebi Defender fun team apapo awon obinrin lórí bọ́ọ̀lù kópa nínu Nations Cup àwọn obìnrin ilé afìko tó wáyé ní ọdún 2016.Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Phoey okech jẹ agbabọọlu lobinrin orile edè Kenya ti a bini 10, oṣu October ni ọdun 1994..
wikipedia
yo
Agbaagba naa ṣere fun Vihiga Queens FC gẹgẹbi midfielderàṣeyọríphoey kopa ninu ere ìdíje CAF awọn obinrin.itọkasi..
wikipedia
yo
Judith Onimbo je agbaboolu lobinrin orile ede Kenya ti a bini 8, osu August ni odun 1999..
wikipedia
yo
Agbáré náà ṣobí gegebi Goràta fún àwọn obìnrin Gaspo.
wikipedia
yo
Nelly sawé je agbaboolu lobinrin orile ede Kenya ti oun sere fun Thika Queens FC gegebi defenkoraseyorinelly kopa ninu Olympic awon obinrin ile Turkey to waye ni odun 2020.itọkasi..
wikipedia
yo
Mohammed Salah jẹ́ àgbàálẹ̀ lọkunrin ti Orilẹ ede Egípití, bakan naa ni osi jẹ agbabọọlu fun Ikọ̀ Liverpool ti liigi Ile-Gẹẹsi ti a mosi Premier League..
wikipedia
yo
Oje ogbontarigi agbabọọlu iwaju fun iko Liverpool, bakan naa ni Captain fun iko orilede Egipti..
wikipedia
yo
ọjẹ agbabọọlu tí a kòle fọwọrọ ni ilẹ Afrika ati ni agbaye lápapọ̀..
wikipedia
yo
Thierry Ndikum/yo (ti a bi ni ojo kerindinlogbon osu keta odun 1997) je elere ije olona jinjin orile - ede Burundi..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2019, o dije ninu mita 10,000 awọn ọkunrin ni Idije Awọn ere-idaraya Agbaye ti 2019 ti o waye ni Doha, Qatar..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2014, o gba ami-eye fadaka ni ìdíje mita 3000 ti awọn ọmọkunrin ni Olimpiiki Igba ooru Ọdun 2014 ti o waye ni NANjing, China..
wikipedia
yo
ní ọdún 2017, ó díje nínú ìdíje àwọn ọkùnrin àgbà ní 2017 IAAF World Cross Country Championship tí ó wáyé ní Kampala, Uganda..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2019, o dije ninu idije awọn ọkunrin agba ni 2019 IAAF World Cross Country Championships ti o waye ni Aarhus, Denmark..
wikipedia
yo
ní ọdún 2019, ó borí ìdíje àwọn ọkùnrin ní Cross Internacional dé là Constitución tí ó wáyé ní Spibendas, Spain.Àwọn itọkasiita ìjápọ àwọn Ọjọ́ìbí ní 1997àwọn ènìyàn Alààyè..
wikipedia
yo
Rodrigue Kwizera (ti a bi ni ọjọ kewa Oṣu Kẹwa Ọdun 1999) jẹ olusare-jinjinna ọmọ orilẹ-ede Burundi kan..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2019, o dije ni ìdíje awọn mita 10,000 awọn ọkunrin ni Idije Awọn ere-idaraya Agbaye ti 2019 ti o waye ni Doha, Qatar..
wikipedia
yo
Ni 2017, o dije ninu idije awọn ọkunrin agba ni 2017 IAAF World Cross Country Championship ti o waye ni Kampala, Uganda..
wikipedia
yo
ní ọdún 2019, ó tún ṣe aṣojú Burundi ní àwọn eré Áfíríkà 2019 tí ó wáyé ní Rabat, Morocco..
wikipedia
yo
ó díje nínú àwọn mítà 5000 àwọn ọkùnrin ó sì parí ní ipò 16th.Àwọn ìtọ́kasíita ìjápọ àwọn Ọjọ́ìbí ní 1999àwọn ènìyàn Alààyè..
wikipedia
yo
Jean-Paul Ghimbare (ti a bi ni ọjọ kejilelogun Oṣu kejila ọdun 1970) jẹ elere-ije ọmọ Ilu Burundi kan ti o ṣe amọja ni ere-ije gigun ati sise jijin.Ghimbare dije ni Olimpiiki Igba ooru 2004 ni Athens nigbati o wo ere-ije, ṣugbọn ko pari ere-ije naa.Awon itọkasi awọn eniyan Alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ni 1970..
wikipedia
yo
Onesphore Nzikwinkunda (ti a bi ni ojo kewa osu Okudu ọdun 1997) jẹ elere ije jinjinna ọmọ orilẹ-ede Burundi, ti o nsa ni mita 5K ati 10K ..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2017, o dije ninu idije awọn ọkunrin agba ni 2017 IAAF World Cross Country Championship ti o waye ni Kampala, Uganda..
wikipedia
yo
ní ọdún 2019, ó díje nínú ìdíje àwọn ọkùnrin àgbà ní 2019 IAAF World Cross Country Championships tí ó wáyé ní Aarhus, Denmark..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2019, ó tún ṣe aṣojú orílẹ̀-èdè Burundi ní àwọn eré Áfíríkà 2019 àti pé ó parí ní ipò 6th nínú mita 10,000 okùnrin.Àwọn Ìtọ́kasíita ìjápọ̀ onesphore Nzikwinkun At World Athletics àwọn ènìyàn Alààyè Eyàwọn Ọjọ́ìbí ní 1997..
wikipedia
yo
ní ọdún 1997, Gashaka gba ami-ẹri fadaka kan ni ere idaraya ni 1997 Jeux de la Francophonie ni awọn mita 10,000.Awon itọkasi awon eniyan Alààyèawon Ọjọ́ìbí ni 1962..
wikipedia
yo
Joslin Sharif Bipfubusa (ti a bi ni ọjọ kewa Oṣu Kẹwa Ọdun 1984) jẹ olukọni bọọlu lati orilẹ-ede Burundi..
wikipedia
yo
Oun na ni alabojuto Burundi lọwọlọwọ.Iṣẹ iṣakoso Bipfubusa ṣakoso Burundi lakoko idije Bangabandhu 2020, ni atẹle ise adase ti o ti ṣakoso Aigle Noir ati ẹgbẹ Burundi labẹ-20 .Awon itọkasi awọn eniyan Aalààyè Ọjọ́ìbí ni 1984..
wikipedia
yo
Alain Olivier Niyungeko (Ti a bi ni ọjọ kewa Oṣu Kẹwa ọdun 1970) jẹ olukọni bọọlu lati orilẹ-ede Burundi, eniti o je oluṣakoso kẹhin ti Burundi .lakoko akoko 2012–13, Niyungeko dari ẹgbẹ agbabọọlu Flambeau de l'Est si akọle Premier League Burundi akọkọ wọn, ọdun mẹta lẹhin idasilẹ..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2016, Niyungeko ni wọn yan gẹgẹ bi oluṣakoso Burundi, ti o rọpo Ahcene ait-Abdelmalek .Awon itọkasi awọn eniyan Alààyèawon Ọjọ́ìbí ni 1970..
wikipedia
yo
Jentx Shikangwa je agbaboolu lobinrin orile ede Kenya ti a bini 27, osu November ni odun 2001..
wikipedia
yo
Agbáré náà ṣobí gegebi For fun Fatih karájì S.Kiboàṣeyọrí. kópa kópa nínú Champions League àwọn obìnrin ìtọ́kasí.
wikipedia
yo
Dorcas ShiKobe jẹ́ agbábọ́ọ̀lù lobinrin ilẹ̀ Kenya tí a Bìní 4, Oṣù April ní ọdún 1989..
wikipedia
yo
Arabinrin naa ṣere gege Defender fun Duquesne FC.aṣeyọridor kopa ninu Nation Cup awọn obinrin ile afituntun to waye ni ọdun 2016.itọkasi..
wikipedia
yo
Cynthia ShilWatso jẹ́ agbábọ́ọ̀lù lobinrin orílẹ̀ ède Kenya tí a Bìní 23, Oṣù July ní ọdún 1999..
wikipedia
yo
Agbáagba náà ṣògbẹ gegebi midfielder fún edf Logroño Base Base kópa nínú Nations àwọn obìnrin àwọn obìnrin afìra tó wáyé ní ọdún 2018.
wikipedia
yo
Dorcas Shiveka je agbaboolu lobinrin ile Kenya ti oun sere gegebi Defender fun Thika Queens FC.Simeonica kopa ninu Cup awon obinrin ile turkeyiyi..
wikipedia
yo