cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Àjẹsára náà a má a ṣiṣẹ́ bó ṣe yẹ nínú gbogbo àwọn oríṣiríṣi àgbéjáde wọ̀nyí.. | wikipedia | yo |
Àjọ Ìlera Àgbáyé gbani nímọ̀ràn láti fúnni ní àjẹsára náà bí ènìyàn bá ti pé ọmọ oṣù mẹ́ẹ̀sán ní àwọn agbègbè ibití àrùn náà ti wọ́pọ̀.. | wikipedia | yo |
Ní àwọn agbègbè ibití àrùn náà kò ti wọ́pọ̀ rárá, fífúnni ní àjẹsára náà bí a bá ti pé ọmọ oṣù méjìlá bá ọgbọ́n mú.. | wikipedia | yo |
A má a wá bíi ìyẹ̀fun gbígbẹ tí a gbọdọ̀ pò kí a tó fúnni yálà sábẹ́ awọ ara tàbí sínú ẹran-ara.. | wikipedia | yo |
Ṣíṣàyẹ̀wò bóyá àjẹsára náà ṣiṣẹ́ lè wáyé nípa ṣíṣe àwọn àyẹ̀wò ẹ̀jẹ̀.Bíi iye àwọn ọmọdé tó tó 85% káàkiri àgbáyé ni ó ti gba àjẹsára yìí ní bí ọdún 2013.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2008, ó kéré, àwọn orílẹ̀-èdè bíi 192 ni wọ́n ń fúnni ní ìwọ̀n egbògi náà méjì.. | wikipedia | yo |
Apapo Àjẹsára arun ita-arun ṣegede-arun Ita Jamini (MMR) di wíwà fun lílò fún igba àkọ́kọ́ ní ọdún 1971.. | wikipedia | yo |
Àjẹsára àrùn Ọ̀fà ṣọnná tàbí ilẹ̀gbóná (chickenìtọ́jú vaccine) di ohun tí a fi kún àwọn mẹ́tẹ̀ẹ̀ta yìí ní ọdún 2005, èyí tó wá di àjẹsára MMRV.. | wikipedia | yo |
Hugo Marston "Hugh" Hefner (1926-2017) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.Ìtọ́kasíàwọn òṣèré fíú ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Edward Leonard "Ed" O'Neill (April 12, 1946) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.Ìtọ́kasíàwọn òṣèré fíú ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Michael Jeter (August 26, 1952 – March 30, 2003) je osere ara Amerika.Ìtọ́kasí osere fíú ara Amerika.. | wikipedia | yo |
Àwọn àjẹsára kòkòrò ará wíwú ènìyàn (H[v) jẹ́ àjẹsára tí ó máa ń dẹ́kun àkóràn tí àwọn irúfẹ́ kòkòrò ará wíwú ènìyàn.. | wikipedia | yo |
Àwọn àjẹsára tí ó wà ń dábọ́bò lòdì sí àwọn irúfẹ́ bóyá méjì, mẹ́rin, tàbí mẹ́sàn tí hpv.. | wikipedia | yo |
Gbogbo àjẹsára ni ó ń dábòbò ó kéré hpv 16 àti 18tí ó ń ṣokùnfà ewu kòkòrò jẹjẹrẹ jẹjẹrẹ obìnrin tí ó léwu jùlọ.. | wikipedia | yo |
àti wọ́ lápapọ̀ pé wọ́n lè dẹ́kun ìdá 70 tí kòkòrò jẹjẹrẹ abẹ́ obìnrin, idà 80 ti kòkòrò jẹjẹrẹ ihò-ìdí, idà 60 ti kọ́kọ́rọ́ ojú ara obìnrin, ìdá 40 ti kòkòrò jẹjẹrẹ ojú ìta ara obìnrin, àti bóyá kòkòrò jẹjẹrẹ ẹnu.. | wikipedia | yo |
Lápapọ̀ wọ́n jùmọ̀ máa ń dẹ́kun àwọn wọnwọ́n ojú-ara pẹ̀lú àwọn àjẹsára lòdì sí irúfẹ́ 4 àti 9 hpv tí ó nṣe ìdábòbò nlá.References.. | wikipedia | yo |
Ian David McsHanhan (September 29, 1942) jẹ́ òṣèré ara Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan.Àwọn ìtọ́kasíàwọn òṣèré fíú ará Britani.. | wikipedia | yo |
Faun wingert (July 4, 1974) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.Ìtọ́kasíàwọn òṣèré fíú ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Gregory Buck "Greg" Kinnear (June 17, 1963) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.Ìtọ́kasíàwọn òṣèré fíú ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Doris May Green (November 4, 1925 – April 17, 2016) jẹ́ òṣèré ara Amẹ́ríkà.Ìtọ́kasí òṣèré fíú ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Glenn Close (March 19, 1947) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.Ìtọ́kasíàwọn òṣèré fíú ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Moscow international business center ránká wọn tún ń pèé ní Moscow-city kápàdé jẹ́ agbèègbè ìṣòwò ní àárín Moscow, Russia.Àwọn àtúnṣeèrèka kúkúrú.. | wikipedia | yo |
Donald Jay "Don" Rickles (May 8, 1926 – April 6, 2017) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.Àwọn ìtọ́kasíàwọn òṣèré fíú ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Broderick Stephen "Steve" Harvey (January 17, 1957) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.Ìtọ́kasí òṣèré fíú ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Àjẹsára dídáranjẹ̀ ọpọlọ ti Japaníìsì jẹ́ àjẹsáratí ń dáàbò bo ni lọ́wọ́ dídáranjẹ̀ ọpọlọ ti Japaníìsì 🙂 | wikipedia | yo |
Ìwọ̀n agbára àwọn àjẹsára náà láti ṣiṣẹ́ ju bíi 90% lọ.. | wikipedia | yo |
Iye àsìkò tí ààbò egbògi náà fi ń wa lára kò tíì fi bẹ́ẹ̀ yẹ ní dáradára, ṣùgbọ́n agbára iṣẹ́ rẹ̀ dàbí èyí tó má a ń dínkù bí àsìkò tí ń lọ síi.. | wikipedia | yo |
A má a ń fúnni yálà bí abẹ́rẹ́ tí a gún sínú ẹran ara ẹni tàbí sábẹ́ awọ ara ẹni.A gbani nímọ̀ràn láti fifúnni gẹ́gẹ́ bí ara àwọn àjẹsára tí a ń gbà lóòrèkóòrè ní àwọn orílẹ̀-èdè tí àrùn náà ti jẹ́ ohun tí ń dà wọ́n láàmú.. | wikipedia | yo |
A má a ń fúnni ní ìwọ̀n egbògi náà kan tàbí méjì, èyí sì dá lé irú àjẹsára náà tí a fúnni.. | wikipedia | yo |
A kìí sábà nílò àfikún ìwọ̀n egbògi náà ní àwọn agbègbè ibi tí àrùn náà ti wọ́pọ̀.. | wikipedia | yo |
Láàárín àwọn ènìyàn tó ní àrùn kògbóògùn HIV/AIDS tàbí àwọn tó lóyún, oríṣi tí a fi kòkòrò afàìsàn àìlèfojúrí tí a ti pa ṣe ni a gbọ́dọ̀ lò.. | wikipedia | yo |
A gba ni nímọ̀ràn láti fún àwọn arìnrìnàjò tó ń gbèrò láti lọ káàkiri ìta-gbangba agbègbè ibi tí àrùn náà ti wọ́pọ̀ ní àjẹsára náà.Àwọn àjẹsára náà kò léwu láti lọ.. | wikipedia | yo |
Ìnira àti rírẹ̀-dòdò lè wáyé ní ojú ibi abẹ́rẹ́ náà.. | wikipedia | yo |
A ṣe àgbéjáde àwọn kan nípasẹ̀ ìlànà DNA aláàtùnkójọpọ̀, àwọn mìíràn nípasẹ̀ kòkòrò afàìsàn àìlèfojúrí tí a ti sọ di aláìlágbára, bẹ́ẹ̀ sì ni àwọn mìíràn jẹ́ nípasẹ̀ kòkòrò afàìsàn àìlèfojúrí tí a ti pa.Àjẹsára dídáranjẹ̀ ti Japaníìsì di ohun tó wà fún lílò fún ìgbà àkọ́kọ́ ní àwọn ọdún 1930. Ó wà lórí Àkójọ Àwọn Egbògi Kòṣeémáàní ti Àjọ Ìlera Àgbáyé, àwọn òògùn tó ṣe pàtàkì jùlọ tí a nílò fún ètò ìleraìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ yòówù yòówù. Ní ilẹ̀ Amẹ́ríkà iye rẹ̀ jẹ́ bíi 100 sí200 200 USD fún ètò ìṣàmúlò egbògi náà lẹ́sẹẹsẹ kanṣoṣo.Àwọn ìtọ́kasí kúkúrú..Àyọkà kúkúrú.. | wikipedia | yo |
Àjẹsára rotavirus jẹ́ àjẹsára tí a fi ń dáàbò bo ara ẹni lọ́wọ́ àkóràn kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn kan tí à ń pè ní rotavirus.. | wikipedia | yo |
Àwọn kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn wọ̀nyí ló má a ń sábà ṣe okùnfà ìgbẹ́ gbuuru tó lágbára púpọ̀ láàárín àwọn ọmọdé.. | wikipedia | yo |
Àjẹsára náà a má a dènà ìwọ̀n 15 sí 34% ìṣẹ̀lẹ̀ ìgbẹ́ gbuuru tó lágbára púpọ̀ náà ní àwọn orílẹ̀-èdè tó sì ń tẹ̀síwájú, àti ìwọ̀n 37 sí 96% ìṣẹ̀lẹ̀ ìgbẹ́ gbuuru tó lágbára púpọ̀ náà ní àwọn orílẹ̀-èdè tó ti ní ìtẹ̀síwájú.. | wikipedia | yo |
Àjẹsára náà dàbí èyí tó má a ń dín ewu ikú tó ti ipasẹ̀ ìgbẹ́ gbuuru wáyé kù láàárín àwọn ọmọdé.. | wikipedia | yo |
Fífún àwọn ọmọ-ọwọ́ ni àjẹsára náà dàbí ohun tó má a ń dín ìṣẹ̀lẹ̀ àrùn náà kù láàárín àwọn àgbàlagbà àti láàárín àwọn tí kò tíì gba àjẹsára náà tẹ́lẹ̀ rí.Àjọ Ìlera Àgbáyé (WHO) gbani nímọ̀ràn pé kí àjẹsára rotavirus jẹ́ ara àwọn àjẹsára tí à ń gbà lóòrèkóòrè, pàápàá júlọ ní àwọn agbègbè ibi tí àrùn náà ti wọ́pọ̀.. | wikipedia | yo |
A gbọ́dọ̀ ṣe èyí ní ìdàpọ̀ pẹ̀lú gbígbé àwọn ohun bíi fífún ọmọ lọ́yàn, fífọ ọwọ́ ẹni, àti lílo omi tó mọ́ àti ìmọ́tótó lárugẹ.. | wikipedia | yo |
Ẹnu ni a ń gbà fúnni ní àjẹsára náà, ènìyàn sì nílò ìwọ̀n egbògi náà méjì sí mẹta.. | wikipedia | yo |
A gbọdọ̀ bẹ̀rẹ̀ sí fúnni láti ìgbà tí ènìyàn bá ti tó ọmọ ọ̀sẹ̀ mẹ́fà.Lílo àjẹsára náà kò léwu.. | wikipedia | yo |
Èyí kan lílò fún àwọn tó ní àrùn kògbóògùn HIV/AIDS pàápàá.Ẹ̀yà ìṣáájú àjẹsára náà níí ṣe pẹ̀lú lọ́pọ̀ ìfun, ṣùgbọ́n ẹ̀yà titun rẹ̀ ní báyìí kò tíì ní ohunkóhun ṣe pẹ̀lú èyí dájúdájú.. | wikipedia | yo |
Nítorí ewu tó le wáyé, a kò gbani nímọ̀ràn láti lòó fún àwọn ọmọ-ọwọ́ tí ìfun wọn ti lò pọ̀ rí.. | wikipedia | yo |
A ṣe àgbéjáde àwọn àjẹsára náà nípasẹ̀ kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn rotavirus tí a ti sọ di aláìlágbára.Àjẹsára náà di èyí tó wà fún lílò ní ilẹ̀ Amẹ́ríkà fún ìgbà àkọ́kọ́ ní ọdún 2006. Ó wà lórí Àkójọ Àwọn Egbògi Kòṣeémáàní ti Àjọ Ìlera Àgbáyé, àwọn òògùn tó ṣe pàtàkì jùlọ tí a nílò fún ètò ìleraìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ yòówù yòówù. Iye owó rẹ̀ lójú pálí jẹ́ bíi 6.96 sí 20.66 USD fún ìwọ̀n egbògi náà kanṣoṣo ní ọdún 2014.. | wikipedia | yo |
Di ọdún 2013 oríṣi àjẹsára náà méjì ni ó wà káàkiri àgbáyé, Rotarix àti rọ́téteq, pẹ̀lú àwọn oriṣi díẹ̀ mìíràn tó tún wà ní àwọn orílẹ̀-èdè kọ̀ọ̀kan.Àwọn Ìtọ́kasíàjẹsára kukuru.. | wikipedia | yo |
SimiṢọlá bọ̀láti Kòsọ́kọ́ tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Simi jẹ́ olórinbìrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Àwọn Àmín-ẹ̀ye tí ó gba àti àwọn tí wọ́n yàn án fúnàwọn ìtọ́kasísẹ̀ (àwọn Ọjọ́ìbí ní 1988àwọn ará Nàìjíríàka Kúdua Aramíràn Araàwọn Ara Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Peter Endmis (December 11, 1967) jẹ́ òṣèré ara Amẹ́ríkà.Ìtọ́kasí òṣèré fíú ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Àjẹsára táífọ́ọ̀dù jẹ́ àjẹsára tí n dènà ibà táífọ́ọ̀dù.. | wikipedia | yo |
Ìwọ̀n agbára wọn tó 30 sí 80% fún bí ọdún mẹ́ta.Àjọ Ìlera Àgbáyé (WHO) gbani nímọ̀ràn pé kí a fúngbogbo àwọn ọmọdé tí ń gbé ní àwọn agbègbè ibi tí àrùn náà ti wọ́pọ̀ ní àjẹsára náà.. | wikipedia | yo |
Bí bẹ́ẹ̀kọ́, wọ́n gbani nímọ̀ràn láti fún gbogbo àwọn tó wà lábẹ́ ewu nlá láti kó àrùn náà ní àjẹsára náà.. | wikipedia | yo |
Ìpolongo nípa Gbígba Àjẹsára ni a tún le lò láti fi ṣàkóso ìtànkálẹ̀ àrùn náà.. | wikipedia | yo |
A gbani nímọ̀ràn láti gba àfikún ìwọ̀n àjẹsára náà láàárín ọdún kọ̀ọ̀kan sí méje-méje, bí a bá wo bí àrùn náà ti wọ́pọ̀ tó ní agbègbè náà. Ní ilẹ̀ Amẹ́ríkà, a gbani nímọ̀ràn láti fún àwọn tó wà lábẹ́ ewú ńlá nìkan, bíi àwọn arìnrìnàjò lọ sí àwọn agbègbè ibi tí àrùn náà ti wọ́pọ̀, ní àjẹsára náà.Àwọn oríṣi àjẹsára náà ti òde-òní kò léwu láti lò rárá.. | wikipedia | yo |
Àwọn àtúnbọ̀tán díẹ̀díẹ̀ lè wáyé ní ojú ibi abẹ́rẹ́ náà.. | wikipedia | yo |
Oríṣi àjẹsára náà tí à n gún fún ní bí abẹ́rẹ́ kò léwu fún àwọn tó ní àrùn kògbóògùn HIV/AIDS láti lò, a sì lè lo oríṣi àjẹsára náà tí à n gba ẹnu fúnni níwọ̀n ìgbà tí ènìyàn náà kò bá tíì ní àmì àrùn náà.. | wikipedia | yo |
Kò tíì yé ni bóyá oríṣi àjẹsára náà tí à n gba ẹnu lò léwu láti lò nígbàtí ènìyàn bá wà nínú oyún.Alràpadà Edward Wright, Richard pfèéffer, àti Wilhelm Kolle ni wọ́n ṣe àgbéjáde àjẹsára táífọ́ọ̀dù àkókò.. | wikipedia | yo |
Nítorí àwọn àtúnbọ̀tán, àwọn àgbéjáde titun àjẹsára náà ni a gbani níyànjú láti lọ.. | wikipedia | yo |
Àwọn àjẹsára táífọ́ọ̀dù wà lórí Àkójọ Àwọn Egbògi Kòṣeémáàní ti Àjọ Ìlera Àgbáyé, àwọn òògùn tó ṣe pàtàkì jùlọ tí a nílò fún ètò ìleraìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ yòówù yòówù iye owó rẹ̀ lójú pálí jẹ́ bíi 4.44 USD fún ìwọ̀n egbògi náà kanṣoṣo ní ọdún 2014.. | wikipedia | yo |
Ní ilẹ̀ Amẹ́ríkà iye owó wọ́n jẹ́ 25 sí 50 USD.Àwọn ìtọ́kasí àjẹsáraÀyọkà kúkúrú.. | wikipedia | yo |
Lorne Cardinal (January 6, 1964) jẹ́ òṣèré ara Amẹ́ríkà.Ìtọ́kasí òṣèré fíú ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
James Eugene "Jim" Carrey (Ọjọ́ mẹ́tàdínlógún Oṣù Kínnín Ọdún 1962) jẹ́ òṣèré, aláwàdà, olùkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà àti Canada.Àwọn ìtọ́kasíàwọn òṣèré fíú ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Jay Scott Greenspan (September 23, 1959) je oṣere ara Amẹrika.itọkasiàwọn oṣere fíú ara Amẹrika.. | wikipedia | yo |
Alan Zweònkọ̀ (May 20, 1950) jẹ́ òṣèré ara Amẹ́ríkà.Ìtọ́kasíàwọn òṣèré fíú ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Michael Adeniyi Aagbọkan Ishola Adénú (Ọjọ́ìbí April Ọdún 1953) jẹ́ oníṣòwò oníṣòwò ajís Ilé-iṣẹ́ Ilé-iṣẹ́ Giya-com | wikipedia | yo |
AOniOniji je ikan ikan omo orile orile ede ti o lowo julo.. | wikipedia | yo |
Ó di olówó láti ibi òwò ne tìwoki `ero alágbéka àti Epoorobi.Àwọn Ìtọ́kasíàwọn oníṣòwò ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Shivaji Rao Gaekwá (Bii ní ọjọ́ kejìlá Oṣù kejìlá ọdún 1950) Wọ́n Tn mọ̀ọ́ sí Rajinikan, jẹ́ òṣèré eré ìtàgé orílẹ̀ èdè Indian tí ó n ṣiṣẹ́ ní ilé iṣẹ́ fíìmù Tamil.. | wikipedia | yo |
Ó ti kópa ninú eré àwọn Bollywood, Telugu, Kannada, Malayalam , Hollywood àti eré ìtàgé ní èdè Bengali.. | wikipedia | yo |
Ó b`ẹr`ẹ eré ìtàgé ṣíṣe nígbà tí ó ń ṣiṣẹ́ olùdarí ọk`ọ p`ẹlú ilé iṣẹ́ ọk`ọ wíwà Bangalore.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 1973, ó darapọ̀ mọ́ ilé `ẹ̀kọ́ Madras Film Institute láti gba oyè diploma nínu eré ìtàgé ṣíṣeàwọn Ìtọ́kasíàwọn Ọjọ́ìbí ní 1950àwọn ènìyàn Alààyèàyọkà kúkurú.. | wikipedia | yo |
Àjẹsára jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ B jẹ́ àjẹsára tí a fi ń dáàbò bo ara ẹni lọ́wọ́ àkóràn kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ B.. | wikipedia | yo |
Ọmọ tuntun a máa gba àkókò abẹ́rẹ́ àjẹsára yìí láàrin wákàtí mẹ́rìndínlógún tí wọ́n bíi àti abẹ́rẹ́ yìí méjì tàbí mẹ́ta lẹ́yìn ìgbà náà.. | wikipedia | yo |
Èyí pẹ̀lú àwọn tí ara wọn kò ní àǹfààní púpọ̀ láti dojú kọ àrùn, bí àwọn tí ó ní àrùn kògbóògùn HIV/AIDS tàbí àwọn tí wọ́n bí lọ́jọ́ àìpẹ́.Lílo àjẹsára yìí déédéé máa ń dáàbò bo èèyàn márundínlọ́gọ̀n nínú ọgọ́rùn èèyàn tí kò ní àrùn.Ṣíṣe àyẹ̀wò ẹ̀jẹ̀ láti ríi dájú wípé àjẹsára yìí ṣiṣẹ́ jẹ́ ohun tí ó ṣe kókó fún àwọn tí ó ní àǹfààní jùlọ láti ní àrùn jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ B.. | wikipedia | yo |
Àfikún abẹ́rẹ́ àjẹsára yìí lè wúlò fún àwọn tí ara wọn kò ní àǹfààní púpọ̀ láti dojú kọ àrùn ṣùgbọ́n kò pọn dandan fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn.. | wikipedia | yo |
Àwọn tí ó ti kó àrùn jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ B ṣùgbọ́n tí wọn kò gba abẹ́rẹ́ àjẹsára yìí gbúdọ̀ gbáà pẹ̀lú àjẹsára tí àwọn Òyìnbó ń pè ní “hepatitis B immune globulin” | wikipedia | yo |
Inú iṣan ni wọ́n maa ń gba abẹ́rẹ́ àjẹsára yìí tí a fi de inú ara.Ewu nípa lílo àjẹsára jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ B ó wọ́pọ̀.. | wikipedia | yo |
Lílò àjẹsára yìí kò léwu nígbà oyún àti nígbà fífún ọmọ lọ́yàn.. | wikipedia | yo |
Kò ní ìbásepọ̀ tí ó dájú pẹ̀lú Guila-ín-Barre syndrome.. | wikipedia | yo |
Wọ́n pelo àjẹsára jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ B tí ó wà báyì nípa ọ̀nà tàbí ọgbọ́n Rebinant DNA.. | wikipedia | yo |
Wọ́n dáwà tàbí pèlú àwọn àjẹsára míràn.Wọ́n fọwọ́sí àjẹsára jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ B àkọ́kọ́ ní ilẹ̀ United States ní ọdún 1981.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ ìkan lára àwọn òògùn tí Àjọ Ìlera Àgbáyé ṣàkójọ ẹ̀ sí òògùn tó wúlò jùlọ fún ìlera.. | wikipedia | yo |
ní bíi 2014, òṣùwọ̀n ọwọ́ rẹ̀ lojú pálí Kuṣi US$ 0.58-13.20 fún abẹ́rẹ́ kan.. | wikipedia | yo |
ní ilẹ̀ Amẹ́ríkà, iye owó rẹ̀ Kúṣì US$50-100.Lílọ fún Ìleraọmọ tuntun ti ìyá tó bá ní àrùn jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ B bá bí a máa gba abẹ́rẹ́ àjẹsára jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ B pẹ̀lú ìlúlbùni.. | wikipedia | yo |
Bayi ọ̀pọ̀lọpọ̀ orílẹ̀ èdè a máa gba abẹ́rẹ́ àjẹsára jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ bfún àwọn ọmọ ìkókó láti den àìsàn jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ B.. | wikipedia | yo |
Ní àwọn orílẹ̀ èdè tí ó ní àǹfààní jùlọ láti ní àrùn jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ B, Gbígba Abẹ́rẹ́ Àjẹsára yí fún ọmọ tuntun ti dínkù àrùn jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ B àti àrùn jẹjẹrẹ inú ẹ̀dọ̀.. | wikipedia | yo |
Wọ́n fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ ní ilẹ̀ Taiwan, níbi tí wọ́n ti ṣètò gbígba abẹ́rẹ́ àjẹsára jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ B kárí gbogbi Àgbáyé ní ọdún 1984 wípé gbígba abẹ́rẹ́ àjẹsára náà má a ń dín ìṣẹ̀lẹ̀ àrùn tí wọ́n ń pè ní lẹ́hìnìwọ̀cellular carcinoma kù láàárín àwọn ọmọdé.Ní ilẹ̀ UK, gbígba abẹ́rẹ́ Àjẹsára Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ b wà lára àyẹ̀wò ìbálòpọ̀ tí wọ́n má ṣe ń fún àwọn ọkùnrin tí ń bá ọkùnrin lòpọ̀ (NA © | wikipedia | yo |
Wọ́n ṣe irú ètò yìí ní orílẹ̀ èdè Ireland.Ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ agbẹ́gebè, gbígba àjẹsára jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ B jẹ́ dandan fún àwọn òṣìṣẹ́ ìlera àti fún àwọn òṣìṣẹ́ ilé àyẹ̀wò fún ìlera.. | wikipedia | yo |
Ilẹ̀ ìṣàkóso àti ìdèNAN ÀRÙN TI ILẸ̀ UNITED States gbani NÍ Ìmọ̀ràn pé Gbígba Abẹ́rẹ́ Àjẹsára Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ B ṣe pàtàkì FÚN ÀWỌN TÓ NÍ ÀRÙN Àtọ̀gbẹ Congresstus.Ipa àkọ́kọ́ gba àjẹsára yìí lẹ́ẹ̀mẹ́ta, Àyẹ̀wò Ẹ̀jẹ̀ le tẹ́lẹ̀ láàárín oṣù kan sí mẹ́rin fún àrídájú iṣẹ́ rẹ̀, tí wọ́n ń pè ní ìdèNAN Àìsàn Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ B LÓJÚ Pẹpẹ Antijẹni, AgbógunGG TÍ Ó TI 100 100/LL Lọ.’ | wikipedia | yo |
Irú ìdáhùn báyìí ma ń wáyé láàárín 85 sí 90% èèyàn.. | wikipedia | yo |
Ìdáhùn AgbógunG tí ó wáyé láàárín 10 sí 100 láàárínkin/LL jẹ́ ìdáhùn tí kò péye.. | wikipedia | yo |
Àwọn èèyàn tí ìdáhùn AgbógunG wọn bá ń ṣiṣẹ́ báyìí mà ń gba ohun tí ó má fún AgbógunGgia yìí lágbára láìsí ìdí fún àyẹ̀wò ẹ̀jẹ̀.. | wikipedia | yo |
Àwọn èèyàn tí ìdáhùn AgbógunG wọn ò pọ́ṣù (tí ìdáhùn AgbógunGòún Wọ́n bá kéré sí 10 láàárínkin/L) gbọdọ̀ ṣe àyẹ̀wò jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ B, wọ́n a sì gba abẹ́rẹ́ abẹ́rẹ́ àjẹsára yìí lẹ́ẹ̀mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn abẹ́rẹ́ àjẹsára ẹ̀ẹ̀kejì, àyẹ̀wò ẹ̀jẹ̀ á tẹ́lẹ̀ láàárín oṣù kan sí mẹ́rin fún àrídájú iṣẹ́ rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Àwọn èèyàn tí ó rí ìyàtọ̀ lẹ́yìn abẹ́rẹ́ àjẹsára Ikeji lè rí ìyàtọ̀tí wọ́n bá gba àjẹsára yìí sára tàbí àfikún ìdá ìdá àjẹsára yìí tàbí ìdá méjì àjẹsára jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ A àti B.. | wikipedia | yo |
Àwọn èèyàn tí ó pàpà rí iyàtọ̀ lẹ́yìn èyí a gba hepatitis B immunoglobulin (HBig) tí wọ́n bá kó àrùn jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ B lọjọ́ wájú.Àwọn ohun tí ó ń ṣe okùnfà ìdáhùn AgbógunG tí ó pọ́ṣùwọ̀n ní tí ọjọ́ orí bá ju ogójì, Ìsanrajù, àti sìgá mímu, àti ọtí mímu pàápàá bí èèyàn bá ní àrùn ẹ̀dọ̀.. | wikipedia | yo |
Àwọn aláìsàn tí Adina àìsàn wọn ó pọ̀ṣù tàbí tí Kinbọ́ọ̀lù wọ́n kò ṣiṣẹ́ dáadáa lè má dáhùn síàjẹsára àjẹsára dáadáa, fífún wọn ní àjẹsára déédéé tí àfikún ìdá àjẹsára yìí lè ṣe wọ́n láánfàní.. | wikipedia | yo |
Okere jù, ìwádì kan fihàn pé iṣẹ́ àjẹsára Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ B kò péye fún àwọn tí ó ní àrùn kògbóògùn HIV.Iye àkọ́kọ́ ìdáàbòbòbáyìí, Ìgbàgbọ́ ti wá pé iye àkọ́kọ́ ìdáàbòbò àjẹsára Jẹ̀dọ̀ B kò Lópin.. | wikipedia | yo |
Síbẹ̀síbẹ̀, tẹ́lẹ̀ ìgbàgbọ́ wa pé iye àkokò tí àjẹsára jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ B lè ṣe ìdáàbòbò mo kò ju bí bí ọdún máàrún sí méje.Àwọn ìtọ́kasíàjẹsára.. | wikipedia | yo |
SPringbo jẹ́ alábọ́dé ẹtù tí wọ́n ń rí ní Gúúsù Áfríkà àti Gúúsù-Wọ-ọ̀run Áfríkà.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ ọ̀kan lára ọmọ ẹgbẹ́ Antidorcas, Jemani onímọ̀ ẹranko AdéHard August Wilhelm von ZIMMERmann ló kọ́kọ́ ṣe àpèjúwe ọmọ ẹbí Boidale yìí ní ọdún 1780.. | wikipedia | yo |