cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Àlàyé ni ó ní pé àwọn ọlọ́run Kidnapped Magec kí ó sì pa ú inú àwọn Teide.. | wikipedia | yo |
Lẹhin ti awọn aye ti wa ni ida sinu òkunkun, ṣugbọn Achaman (ọrun Ọlọrun) ati ki o tu u ni fẹ́un ni ibi guayotaguancheste.. | wikipedia | yo |
Santa Cruz dé Tenerife ní a ìlú lórí erékùṣù ti Tenerife.. | wikipedia | yo |
O ti wa ni olú-àwọn Erékùṣù Kanari ati àwọn ẹkùn ti Santa Cruz dé Tenerife.. | wikipedia | yo |
Ó ní ó ní olùgbé tí a 203.811 Olugbé.Àwọn Erékùṣù Kanariàwọn oluilu ní Europe.. | wikipedia | yo |
Chaxiraxi ni iya orisa si atijọ olugbe ti awọn erekuṣu ti Tenerife (awọn erekuṣu kanari), awọn guanches npe ni.. | wikipedia | yo |
Ni awọn Ijo Katoliki Esin a ti dámọ pẹlu awọn virgen de canDelaria, ì̀ṣàis ti àwọn àwọn Erekusu Kanariguan..an.. | wikipedia | yo |
Àjẹsára àrùn dìgbòlugi jẹ́ àjẹsára tí à ń lò láti fi dènà àrùn dìgbòlugi. Àwọn oríṣiríṣi wọn wà tí a lè lò láìséwu, tí wọ́n sì ń ṣiṣẹ́ bọ̀ ti yẹ.. | wikipedia | yo |
A lè lò wọ́n láti fi dènà àrùn dìgbòlugi ṣáájú tabi fún àkókò díẹ̀ lẹ́yìn tí eniyan bá ti wà ní sàkání ibití kòkòrò àrùn rẹ̀ gbé wá, bíi kí ajá tabi àdán gé ni jẹ.. | wikipedia | yo |
Agbára àti kojú àìsàn tí ènìyàn yóò ní jẹ́ èyítí yóò pẹ́ títí lẹ́yìn tí ènìyàn bá ti gba ìwọ̀n egbògi náà mẹ́ta.. | wikipedia | yo |
A má a ń sábà fún ni ní àwọn àjẹsára náà nípasẹ̀ abẹ́rẹ́ tí à ń gùn sínú àwo tàbí ẹran ara ẹni.. | wikipedia | yo |
Leyin ti eniyan ba ti wa ni sàkání ibití kòkòrò arun re gbe wa, a ma a n saba gba àjẹsára naa pelu awon akoonu inu ẹjẹ ti ngbógun ti awonkòkòrò arun ninu ara ti arun dìgbòlugi.. | wikipedia | yo |
A gba ni níyànjú láti fún àwọn tó wà lábẹ́ ewu wíwà ní sàkání ibití àrùn náà gbé wà ní àjẹsára kí wọ́n tó lọ sí irú sàkání bẹ́ẹ̀.. | wikipedia | yo |
Àwọn àjẹsára náà a má a ṣiṣẹ́ lára ènìyànàti lára àwọn ẹranko mìíràn.. | wikipedia | yo |
Gbígba àjẹsára fún ajá jẹ́ ìgbésẹ̀ tó lágbára láti dènà àrùn náà lára ènìyàn.A lè lò wọ́n láìséwu fún ẹnikẹ́ni pẹ̀lú ọjọ́-orí yòówù.. | wikipedia | yo |
Iye àwọn ènìyàn tó tó 35 sí 45 nínú ọgọ́ọ̀rún a má a ní ìrírí pípupa yóò àti dídùnní ojú ibi abẹ́rẹ́ náà fún ìwọ̀n ìgbà díẹ̀.. | wikipedia | yo |
Iye àwọn ènìyàn tó tó 5 sí 15 nínú ọgọ́ọ̀rún lé ní ibà, ẹ̀fọ́rí, tàbi kí èébì má a gbé wọn.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn tí ènìyàn bá ti wà ní sàkání ibití ènìyàn ti lè kó àrùn dìgbòlugi, kò sí ohun tó ní kí ènìyàn má gba àjẹsára náà. Púpọ̀ lára àwọn àjẹsára náà kò ní ohun tí à ń pè ní Thimèrò nínú.. | wikipedia | yo |
Àwọn àjẹsára tí a ṣe pẹ̀lú iṣan-ara ni à ń lò ní àwọn orílẹ̀-èdè mẹ́èlò kan, pàápàá ní Esia àti Latin Amẹ́ríkà, ṣùgbọ́n agbára wọn kò pọ̀ púpọ̀, bẹ́ẹ̀ sì ni àtúnbọ̀tán wọn pọ̀ púpọ̀.. | wikipedia | yo |
Nítorí náà ni Àjọ Ìlera Àgbáyé kò ṣe gba ni nímọ̀ràn láti má a lò wọ́n.Àìmọye ènìyàn káàkiri àgbáyé ni a ti fún ní àjẹsára náà, a sì mọ̀ pé èyí a má a dáàbò bo iye àwọn ènìyàn tó ju 250,000 lọ lọ́dún.. | wikipedia | yo |
Iye owó rẹ̀ lójú pálí jẹ́ 44 sí 78 USD fún ètò ìtọ́jú lẹ̀ẹ̀kanṣoṣo ní ọdún 2014.. | wikipedia | yo |
Ní ilẹ̀ Amẹ́ríkà ètò ìtọ́jú lẹ̀ẹ̀kanṣoṣo ti àjẹsára dìgbòlugi ju 750 USD lọ.References.. | wikipedia | yo |
Àwọn àjẹsára àrùn onígbá jẹ́ àwọn àjẹsára tó ní agbára láti dènà àrùn onígbá .. | wikipedia | yo |
ìwọ̀n agbára wọn tó bíi 85% ní oṣù mẹ́fà àkọ́kọ́ lẹ́yìn tí ènìyàn gbà wọ́n, àti 50-60% lẹ́yìn ọdún kan.. | wikipedia | yo |
Ìwọ̀n agbára wọn a má a dínkù sí ìwọ̀n tó kéré sí 50% lẹ́yìn ọdún méjì.. | wikipedia | yo |
Bí a bá ti fún iye àwọn ènìyàn tó pọ̀ púpọ̀ láàárín àwùjọ kan ní àjẹsára náà, àǹfàní tó wà nínú ààbò lọ́wọ́ àrùn tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn àwùjọ kan ní lè wáyé láti dáàbò bo àwọn tí kò tíì gba àjẹsára náà.. | wikipedia | yo |
Àjọ Ìlera Àgbáyé gba ní nímọ̀ràn láti lò wọ́n pẹ̀lú àwọn ìgbésẹ̀ mìíràn tí a lè gbé fún àwọn tó wà lábẹ́ ewu ńlá láti kó àrùn náà.. | wikipedia | yo |
Ìwọ̀n egbògi náà méjì tàbí mẹ́eta, tí à ń gba ẹnu lò, ni a má a ń sábà dámọ̀ràn. Àwọn oríṣi tí a lè fún ní bí abẹ́rẹ́ náà wà ní àwọn agbègbè kan ní àgbáyé ṣùgbọ́n wọn kò fi bẹ́ẹ̀ wọ́pọ̀.Àwọn oríṣi àjẹsára náà méjèèjì tó wà, tí à ń gba ẹnu lọ, ni a lè lò láìséwu.. | wikipedia | yo |
Inú-rírun tàbí ìgbé-yíya tí kò fi bẹ́ẹ̀ ni ipa lè wáyé.. | wikipedia | yo |
Wọ́n ṣeé lò láìséwu bí ènìyàn bá ní oyún, bẹ́ẹ̀ sì ni àwọn tí agbára àti kojú àìsàn wọn kò múnádóko náà tún lè lò ó. A fún ni ní ìwé-àṣẹ láti lò wọ́n ní àwọn orílẹ̀-èdè tó ju 60 lọ.. | wikipedia | yo |
imulo rẹ ni awọn orilẹ-ede ti arun naa ti wọpọ a ma a mu abajade ti a lero waye.Awon àjẹsára akọkọ ti a lo lati koju arun onigbameji ni a se agbejade won ni ipari awon odun 1800.. | wikipedia | yo |
Àwọn ló jẹ́ àjẹsára àkọ́kọ́ tí a lọ káàkiri jùlọ, tí a ṣe àgbéjáde rẹ̀ ní yàrá tí a ti ń ṣe àgbéjáde àwọn egbògi. A ṣe àgbéjáde àwọn àjẹsáratí a ń gba ẹnu lọ ní àwọn ọdún 1990.. | wikipedia | yo |
Ó wà lórí Àkójọ Àwọn Egbògi Kòṣeémáàní ti Àjọ Ìlera Àgbáyé (World Health Organization), àwọn òògùn tó ṣe pàtàkì jùlọ tí a nílò fún ètò ìleraìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ yòówù. Iye owó tí a nílò láti dáàbò bo ara ẹni lọ́wọ́ àrùn onígbá jẹ́ láàárín 0.1 sí 4.0 USD. | wikipedia | yo |
Àwọn àjẹsára àrùn rọpárọsẹ̀, jẹ́ àwọn àjẹsára tí a ń lò láti dènà àrùn rọpárọsẹ̀ (adéaláàánú).. | wikipedia | yo |
À ń lo kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn rọpárọsẹ̀ tí a ti pa láti fi ṣe oríṣi kan, a sì má a ń fún ni ní èyí bíi abẹ́rẹ́ (IPv), a sì tún ń lo kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn rọpárọsẹ̀ tí kò lágbára mọ́ láti fi ṣe oríṣi kejì, a sì ń gba ẹnu lọ èyí (òpv).. | wikipedia | yo |
Àjọ Ìlera Àgbáyé gba ní níyànjú pé kí gbogbo ọmọdé má a gba àjẹsára àrùn rọpárọsẹ̀. Àwọn àjẹsára méjèèjì náà ti dẹ́kun àrùn rọpárọsẹ̀ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ orílẹ̀-èdè àgbáyé, wọ́n sì ti dín iye ènìyàn tó ń ní àrùn náà lọ́dọọdún kù láti iye tí a ṣírò sí 350,000 ní ọdún 1988 sí 359 ní ọdún 2014.Àwọn àjẹsára àrùn rọpárọsẹ̀ tí a fi kòkòrò tí a ti pa ṣe náà kò léwu rárá.. | wikipedia | yo |
Pípọn yoo ibi ojú abẹ́rẹ́ náà àti ìrarán dídí lè wáyé.. | wikipedia | yo |
Àjẹsára àrùn rọpárọsẹ̀ tí a ń gba ẹnu lọ a má a ṣe okùnfà àrùn rọpárọsẹ̀ tó níí ṣe pẹ̀lú ìmúlò àjẹsára náà nínú ìwọ̀n egbògi náà tó tó méẹ́tá mílíọ́nù kan.. | wikipedia | yo |
A lè lo oríṣi àjẹsára méjèèjì náà láìséwu bí ènìyàn bá ni oyún àti bí ènìyàn bá ní àrùn kògbóògùn HIV/AIDS ṣùgbọ́n tí ara rẹ̀ sì dá ṣáká.Àjẹsára àrùn rọpárọsẹ̀ àkọ́kọ́ níàjẹsára àrùn rọpárọsẹ̀ tí a fi kòkòrò tí a ti pa ṣe.. | wikipedia | yo |
Enití ó se àgbéjáde rẹ̀ ní Jonas Salk , a sì bẹ̀rẹ̀ síí lòó ní ọdún 1955. Ẹnití ó ṣe àgbéjáde àjẹsára àrùn rọpárọsẹ̀ tí à n gba ẹnu lọ ní Albert ṣàbìn, a sì bẹ̀rẹ̀ sí tàá fún lílò ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ní ọdún 1961. Wọ́n wà lórí Àkójọ Àwọn Egbògi Kòṣeémáàní ti Àjọ Ìlera Àgbáyé, àwọn òògùn tó ṣe pàtàkì jùlọ tí a nílò fún ètò ìleraìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ yòówù.. | wikipedia | yo |
Iye owó rẹ̀ lojú pálí jẹ́ bíi 0.25 USD fún ìwọ̀n egbògi náà kanṣoṣo fún oríṣití à ń gba ẹnu lọ ní ọdún 2014.. | wikipedia | yo |
Ní ilẹ̀ Amẹ́ríkà iye owó rẹ̀ jẹ́ 25 sí 50 USD fún oríṣi tí a fi kòkòrò tí a ti pa sẹ.References.. | wikipedia | yo |
Àjẹsára ibà pọ́njú-pọ́ntọ̀ jẹ́ àjẹsára tí ń dáàbò bò ní lọ́wọ́ ibà pọ́njú-pọ́ntọ̀. Ibà pọ́njú-pọ́ntọ̀ jẹ́ àkóràn àrùn kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn tó má a ń sábà wáyé ní Áfríkà àti Gúsù Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Iye àwọn ènìyàn tó tó 99% ni ó má a ń ní agbára àti kojú àrùn náà láàárín oṣù kan lẹ́yìn tí wọ́n bá ti gba àjẹsára náà, èyí sì dàbí ẹni pé yóò wà títí ayé wọn.. | wikipedia | yo |
À ń fún ni gégé bí abẹ́rẹ́ tí a gún sínú ẹran ara ẹni tàbí tí a gún sábẹ́ awọ ara ẹni.Àjọ Ìlera Àgbáyé (WHO) gba ni nímọ̀ràn láti má a gba àjẹsára lóòrèkóòrè ní gbogbo orílẹ̀-èdè tí àrùn náà ti wọ́pọ̀.. | wikipedia | yo |
Èyí gbọdọ̀ wáyé láàárín àkókò tí ènìyàn jẹ́ ọmọ oṣù mẹ́ẹ̀sán sì Meẹ̀wá.. | wikipedia | yo |
Àwọn ènìyàn tó n rin ìrìn-àjò lọ sí àwọn agbègbè ibití àrùn náà ti n wáyé ni a tún gbọ́dọ̀ fún ní àjẹsára náà. A kìí sábà nílò àfikún ìwọ̀n àjẹsára náà lẹ́yìn èyítí a bá ti kọ́kọ́ fun ni.Àjẹsára ìbá pọ́njú-pọ́ntọ̀ jẹ́ èyítí kò léwu rárá.. | wikipedia | yo |
Èyí rí bẹ́ẹ̀ fún àwọn tó ní àkóràn àrùn HIV ṣùgbọ́n tí wọ́n kò ní àmì àrùn náà pàápàá.. | wikipedia | yo |
Àtúnbọ̀tán wọ́ọ́rọ́wọ́ tó lè wáyé ní orí-fífọ́, ìrora nínú ẹran ara, ìrora lójú ibi abẹ́rẹ́, ibà, àti ará-sísú.. | wikipedia | yo |
Gbígbọ́ egbògi lára ẹni a má a wáyé ní mẹ́kóejò nínú mílíọ̀nù ìwọ̀n egbògi náà, ìṣòro tó lágbára tó níí ṣe pẹ̀lú iṣan ara náà a má a wáyé ní mẹ́ẹ̀rín nínú mílíọ̀nù ìwọ̀n egbògi náà, bẹ́ẹ̀ sì ni ìkùnà àwọn ẹ̀yà tí ṣíṣe oríṣiríṣi nínú ara náà a má a wáyé ní mẹ́ẹ́tà nínú mílíọ̀nù ìwọ̀n egbògi náà.. | wikipedia | yo |
Ó ṣeé ṣe kí ó máṣe léwu láti lòó nígbàtí ènìyàn bá ní oyún, nítorí náà, a dámọ̀ràn lílọ rẹ̀ láàárín àwọn ènìyàn tó lè wà ní sàkání ibití àrùn náà tí ń ràn ní.. | wikipedia | yo |
A kò gbọ́dọ̀ lọọ fún àwọn tí agbára ìyìn àrùn wọn kò bá múnádóko.A bẹ̀rẹ̀ ìmúlò àjẹsára iba pọ́njú-pọ́ntọ̀ ní ọdún 1938.. | wikipedia | yo |
Ó wà lórí Àkójọ Àwọn Egbògi Kòṣeémáàní ti Àjọ Ìlera Àgbáyé, àwọn òògùn tó ṣe pàtàkì jùlọ tí a nílò fún ètò ìlera ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ yòówù.. | wikipedia | yo |
Iye owó rẹ̀ lojú pálí jẹ́ 4.30 sí21.30.30 USD fún ìwọ̀n egbògi náà kanṣoṣo ní ọdún 2014.. | wikipedia | yo |
A ṣe àgbéjáde àjẹsára náà pẹ̀lú àwọn kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn iba pọ́njú-pọ́ntọ̀, àwọn èyítí a ti sọ di aláìlágbára.References.. | wikipedia | yo |
Nadia Pariss (Ọjọ́ìbí Oṣù Kínní 1, 1990) je omo Áfríkà Amẹ́ríkà Ara awon Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Aṣọ̀kan. Ori'BOAtọ́kasí Welcome to Nadias Pariss Nadia Pariss ni Internet adult Film Database Pariss ni adult Film Database Nadia Nadia Pariss ni define Sexy Bá 2019 Ara Améka Ọmọ Áfríkàlola Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Joseph "Joe" Magves (December 8, 1955) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.Ìtọ́kasíàwọn òṣèré fíú ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Bradley "Brad" Leláyà je osere ara Amerika.Ìtọ́kasí osere fíú ara Amerika.. | wikipedia | yo |
quire FriDell (February 9, 1943) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.Ìtọ́kasíàwọn òṣèré fíú ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Robert "King" Roridy (6 Oṣù kejìlá, 1929 – February 7, 2001) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.Ìtọ́kasí òṣèré fíú ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
(August 31, 1923– – July 7, 1989) je osere ara Amerika.Àwọn oṣere fíú ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Paul lórin Kantner (17 Oṣù Kẹta, 1941 – January 28, 2016) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.Ìtọ́kasí òṣèré fíú ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Shia ṣàìdé LaBebù (June 11, 1986) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.Ìtọ́kasí ̀ga fíú ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Joseph Francis "Joe "Alavkey III (April 17, 1952 – February 3, 2016) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.Ìtọ́kasí òṣèré fíú ará Kánádà.. | wikipedia | yo |
Àjẹsára ṣegedea má a dènà àrùn ṣegedeṣegede. Bí a bá lòó fúnọ̀pọ̀lọpọ̀, wọ́n má a má dín ìnira àrùn náà kù láàárín àwùjọ náà láàárín àwùjọ rẹ̀.Ipá rẹ̀ bí a bá lòó fún ìwọ̀n ènìyàn tó tó 90% láàárín àwùjọ kan ní bíi 85% sí 85% ìwọ̀n egbògi náà méjì ní a nílò láti dènà àrùn náà fún ìgbà pípẹ́ sínú pípẹ́ ní ìgbà pípẹ́ ní ìgbà pípẹ́ ní a nílò ní Mo sì ní ìgbà pípẹ́ ní sì ní gbogbo ní Mo ní sì ní ìgbà ní sì ní gbogbo tó ní Mo bá kọ́ tó ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ náà ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ tí ó ní gbogbo ní apá ìnira ní Mo ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ náà ní sì ní apá tó ní orí rẹ̀ ní sì ní sì ní bíi àwùjọ ní bíi àwùjọ kan ní bíi ‘Ó ní ó nílò ní Mo ní Mo ní ilé pípẹ́ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ kan ní bíi 85.[4] Orí ìnira tí a nílò láti dènà ní bá ní sì dènà ní gbogbo tó lè dènà ní ìwọ̀n ènìyàn tó ní ojú àwùjọ kan ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ kan ní gbogbo àrùn àti oríṣi náà dín náà àti a nílò ní àwọn dènà àrùn náà ní bí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn tó ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ kan ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìnira kan ní àpapọ̀ náà ló ní sì ní orí náà ní * ní ìlera náà ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ tó ní tó ní tó ní pẹ̀lú pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ kan ní a kan ní òkè kan ní a nílò sí*_ | wikipedia | yo |
Ìwọ̀n egbògi àkọ́kọ́ ni a dámọ̀ràn fún lílò láàárín ìgbà tí ènìyàn bá ti pé ọmọ oṣù 12 sí 18.. | wikipedia | yo |
Ìwọ̀n egbògi kejì ni a ó ò fúnni láàárín ìgbà tí ènìyàn bá di ọmọ ọdún méjì sí ọmọ ọdún mẹ́ẹ́fà. Lílò rẹ̀ lẹ́yìn tí ènìyàn bá ti wà ní sàkání ibití àrùn náà ti wáyé, fún àwọn tí kò tíì níagbára àti kojú àrùn tẹ́lẹ̀, jẹ́ ohun tí yóò wúlò púpọ̀.Àjẹsára púpọ̀ jẹ́ èyítí kò léwu láti lò láti lọ àtúnbọ̀tán rẹ̀ kìí sì ní ipá rárá. Ó lè fa ìrora pẹ̀lú wíwú ojú wíwú ojú ibi abẹ́rẹ́, àti ìba díẹ̀.. | wikipedia | yo |
Àwọn àtúnbọ̀tán tó burú ju ìwọ̀nyí lọ kò wọ́pọ̀. Kò sí ẹ̀rí tó tó láti so àjẹsára náà pọ̀ mọ́ ìnira tó jẹ mọ́ àwọn àìsàn inú iṣan-ara. A kò gbọdọ̀ fúnàwọn tó ní oyún tàbí tí agbára àti kojú àkóràn àìsàn wọn ti dínkù pátápátá níàjẹsára náà. Àjọ tó burú láàárín àwọn ọmọ tí ìyá tí ìyá wọn gbaàjẹsára náà nígbà tó lóyún; ní a kò ní àkọsílẹ̀ kankan nípa rẹ̀. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé a pilẹ̀ àjẹsára náà nínú sẹ́ẹ̀lì adìẹ, a lè lòó fún àwọn tó ní ìfèsì ara lọ́nà sí ẹ̀yìn sí ẹ̀yin tó sí ẹ̀yìn-èdè tó ti ní ọ̀pọ̀ lára àwọn orílẹ̀-èdè tó sí àwọn orílẹ̀-èdè tó ń tẹ̀síwájú a fikún ara ètò àjẹsára wọn, nígbà púpọ̀, ní ìdàpọ̀ pẹ̀lú àjẹsára ìta, àti ti gbogbo ìta (me (àrùn) tí gbogbo ìta ti inú ìta tí a mọ sí MMR.. | wikipedia | yo |
Àdàlù àwọn mẹ́tẹ̀ẹ̀ta yìí pẹ̀lú àjẹsára varicella (kòkòrò àrùn àìlèfojúrí tí ń fa ọfà ṣọ̀pọ̀nná tàbí ilẹ̀gbóná) tí a mọ̀ sí MMRV náà wà pẹ̀lú. Ní ọdún 2005 orílẹ̀-èdè 110 ni ó pèsè àjẹsára náà ní oríṣi yìí.. | wikipedia | yo |
Ní àwọn agbègbè tí a ti ń fún àwọn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ní àjẹsára náà, ìwọ̀n ìtànkálẹ̀ àrùn náà ti dínkù sí iye tó ju 90% lọ.. | wikipedia | yo |
Ó fẹ́rẹ̀ tó ìdajì bílíọ̀nù ìwọ̀n oríṣi àjẹsára náà kan tí a ti fún àwọn ènìyàn.A fúnni ní ìwé-àṣẹ àkọ́kọ́ fúnàjẹsára ṣegedeṣegede ní ọdún 1948; ṣùgbọ́n èyí kò ṣiṣẹ́ fún ìgbà pípẹ́.Àwọn àjẹsáratí tí a mú dára síwájú síi di ohun tó wà fún lílòọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ní àwọn ọdún 1960.. | wikipedia | yo |
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àjẹsára àkọ́kọ́ jẹ́ oríṣi tí a fi kòkòrò afàìsàn àìlèfojúrí tí a ti pa ṣe, àwọn àgbéjáde tó tẹ̀lé èyí jẹ́ àwọn tí a fi kòkòrò afàìsàn àìlèfojúrí tó ṣì wà láàyè, ṣùgbọ́n tí a ti sọ di aláìlágbára, ṣe.. | wikipedia | yo |
Ó wà lórí Àkójọ Àwọn Egbògi Kòṣeémáàní ti Àjọ Ìlera Àgbáyé, àwọn òògùn tó ṣe pàtàkì jùlọ tí a nílò fún ètò ìleraìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ yòówù. Àwọn oríṣiríṣi rẹ̀ ni ó ti wà fún lílò láti bíi ọdún2007. | wikipedia | yo |
Fífún ní níàjẹsára nígbàtí ènìyàn bá ní oyún lè dáàbò bo ọmọ inú oyún náà.A a ṣe ìṣirò pé àjẹsára náà ti dáàbò bo iyeẹ̀mí tó ju ìdajì mílíọ̀nù òmíràn lọ ní ọdún2002.Àjọ Ìlera Àgbáyéàti ilẹ̀-iṣẹ́ ìṣàkósoàti àti ìdènà àrùn gba ni nímọ̀ràn pé kí a fún gbogbo ọmọdé ní àjẹsára ikọ́ọfe, àti pé kí a fikún àwọn àjẹsáratí a ngbà lóòrèkóòrè. Èyí sì kan tó ní àrùn kògbóògùn/AIDS kògbóògùn HIV/AIDS pàápàá.. | wikipedia | yo |
Ìwọ̀n egbògi meeta tí a bẹ̀rẹ̀ lọ́gán tí ọmọ bá ti pé ọmọ ọ̀sẹ̀ mẹ́ẹ́fà ni a má a ń sábà dámọràn fún àwọn ọmọdé kékèké.. | wikipedia | yo |
A lè fún àwọn ọmọ tó ti dàgbà díẹ̀ síi àti àwọn àgbàlagbà ní àfikún ìwọ̀n egbògi.. | wikipedia | yo |
Àjẹsára náà wà gẹ́gẹ́ bí àdàlú pẹ̀lú àwọn àjẹsára mìíràn nìkan.Àwọn àjẹsára aláìní sẹ́ẹ̀lì ni a má a ń sábà lò ní àwọn orílẹ̀-èdè tó ti ní ìlọsíwájú nítorí àtúnbọ̀tán rẹ̀ tí kò ní ipá púpọ̀.. | wikipedia | yo |
Ibi Ojú Abẹ́rẹ́ Lára Iye Àwọn Ènìyàn Tó Tọ́ 10 sí 50% tí a fún ní Àjẹsára Adéamọ̀nà Sẹ́ẹ̀lì a má a pupa yòò, wọ́n a sì má a ní ìba.. | wikipedia | yo |
gírì àti ìgbé-kíké fún ìgbà pípẹ́ a má a wáyé lára iye àwọn ènìyàn tó kéré sí ìwọ̀n kan nínú ọgọ́ọ̀rún.. | wikipedia | yo |
Pẹ̀lú àjẹsára aláìní sẹ́ẹ̀lì, apá-wíwú tí kò ní ni lára rárá lè wáyé fún àkókò díẹ̀.. | wikipedia | yo |
Àtúnbọ̀tán pẹ̀lú àwọn oríṣi àjẹsára náà méjèèjì, pàápàá jùlọ pẹ̀lú àjẹsára Adével Sẹ́ẹ̀lì, a má a kéré síwájú síi bí ọjọ́-orí ọmọ bá ti kéré sí.. | wikipedia | yo |
A kò gbọdọ̀ lo àjẹsára idì sẹ́ẹ̀lì fún ọmọ tí ọjọ́-orí rẹ̀ bá ti kọjá ọdún mẹ́ẹ́fà.. | wikipedia | yo |
Kò sí ìṣòro ọlọ́jọ́-pípẹ́ tó jẹ mọ́ àìsàn nínú iṣan ara pẹ̀lú rakeèyí nínú àwọn àjẹsára méjèèjì.A ṣe àgbéjáde àjẹsára ikọ́ọfe ní ọdún 1926.. | wikipedia | yo |
Iye owó ẹ̀yà rẹ̀ kan tó tún ní àwọn àjẹsára àwàlú ẹyìn, ikọ́ gbẹ̀fun gbẹ̀fun, àrùn rọpárọsẹ̀, àti ti ọ̀fìnkì oríṣi b nínú jẹ́ 15.41 USD fún ìwọ̀n egbògi náà kanṣoṣo ní ọdún 2014.References.. | wikipedia | yo |
Àjẹsára ọ̀fìnkì oríṣi b tí kòkòrò àrùn HaII ń fà jẹ́ àjẹsára tí ń lò láti dènà àkóràn ọ̀fìnkì oríṣi b tí kòkòrò àrùn Ha69 ń fa (Hib).. | wikipedia | yo |
Ní àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n ti kàá kún ara àjẹsára tí à ń lò lóòrèkóòrè, iye àkóràn àrùn Hib tó ní ipa ti dín kù pẹ̀lú ìwọ̀n tó ju 90% lọ.. | wikipedia | yo |
Èyí sì ti mú kí àwọn àrùn bíi dídáranjẹ̀ awọ fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ tó bo ọpọlọ àti ọ̀pá-ẹ̀yìn (meningitis), dídáranjẹ̀ ẹ̀dọ̀fóró (Jaini), àtidídáranjẹ̀ Belu Belu- (epihias) dín kù lọ́pọ̀lọpọ̀.Àjọ Ìlera Àgbáyéàti Ilé-iṣẹ́ Ìṣàkóso àti Ìdènà Àrùn fọwọ́sí ìmúlò rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ìwọ̀n egbògi náà méjì tàbí mẹ́eta ni a gbọdọ̀ fún ènìyàn kí ó tó pé ọmọ oṣù mẹ́ẹ́fà.. | wikipedia | yo |
Ìwọ̀n egbògi àkọ́kọ́ ni a gba ni nímọ̀ràn láti gbà bí ènìyàn bá ti ń pé ọmọ ọ̀sẹ̀ mẹ́ẹ́fà, èkejì sì gbọdọ̀ wáyé níọ̀sẹ̀ kẹẹ̀rin sí àsìkò yìí.. | wikipedia | yo |
Bí ó bá jẹ́ ìwọ̀n àjẹsára náà méjì péré ni a fún ni, a gba ni nímọ̀ràn láti gba ìwọ̀n àjẹsára náà mìíràn lọ́jọ́ iwájú.. | wikipedia | yo |
A má a ń gbàá gẹ́gẹ́ bí abẹ́rẹ́ tí a gún sínú ẹran-ara ẹni.Àtún tó ní ipá kò fi bẹ́ẹ̀ wọ́pọ̀.. | wikipedia | yo |
Iye àwọn ènìyàn tó tó 20 sí 25% a má a ní ìrora ní ojú ibi abẹ́rẹ́ náà, àwọn bíi 2% a sì má a ní ìba.. | wikipedia | yo |
A kò rí ẹ̀rí tó fihàn kedere pé àjẹsára náà ní ohunkóhun ṣe pẹ̀lúìfèsì ara ẹni lọ́nà òdì sí ohun tí ènìyàn kóríra – | wikipedia | yo |
Àjẹsára Hib wà gẹ́gẹ́ bí èyí tó dádúró, bí èyí tó jẹ́ àdàlù pẹ̀lúàjẹsára ikọ́ gbẹ̀fun-Àwa/Àwa/àwa Ẹ̀yin, àti bí èyí tó jẹ́ àdàlù pẹ̀lú àjẹsára Ìbàra jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ Oríṣi B, láàárín àwọn oríṣiríṣi mìíràn.. | wikipedia | yo |
Gbogbo àwọn àjẹsára Hib tí a n lo báyìí jẹ́ àjẹsára alaáṣòpò.Àjẹsára Hib àkọ́kọ́ ni a ṣe jáde ní ọdún 1977, èyí tí a rọ́pò pẹ̀lú àgbéjáde mìíràn tí nṣiṣẹ́ dáradára jùú ló ní àwọn ọdún 1990.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2013, orílẹ̀-èdè 184 ni wọ́n fi sí ara àwọn àjẹsára oorekòòré wọn.. | wikipedia | yo |
Iye owó rẹ̀ lojú pálí fúnàjẹsára tó ní ojú ibi àsopọ̀ máàrún, ọ̀kan lára èyítí ó jẹ́ Hib, jẹ́ 15.40 USD fún ìwọ̀n egbògi náà kanṣoṣo ní ọdún 2014.. | wikipedia | yo |
Ní ilẹ̀ Amẹ́ríkà iye owó rẹ̀ jẹ́ bíi 25 sí 50 USD fún ìwọ̀n egbògi náà kanṣoṣo.Àwọn ìtọ́kasíàyọkà kúkúrú.. | wikipedia | yo |
Àjẹsára ọ̀fìnkì, tí a tún mọ̀ sí abẹ́rẹ́ ọ̀fìnkì, jẹ́ àjẹsára tí ń dáàbò bò ní lọ́wọ́ ọ̀fìnkì.. | wikipedia | yo |
A má a ń ṣe àgbéjáde ẹ̀yà àjẹsára náà titun lẹ́ẹ̀mejì lọ́dún nítorí tí kòkòrò àrùn àìlèfojúrí afàìsàn ọ̀fìnkì a má a paradà kíákíá.. | wikipedia | yo |