cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ọkọ osere lobinrin keji George Langford kú lórí egbò ìbọn ní oṣù January ọdún 1925 ni ko pẹ tí wọ́n fẹ́ ara wọn.Hòkò fẹ́ James Lloyd Crawford ní oṣù March 21 ọdún 1941 tí wọ́n sì pínyà ní ọdún 1945 lẹ́yìn ìgbéyàwó ọdún mẹ́rin àbọ̀.HÚN fẹ́ Larry Williams ní oṣù June 11 ní ọdún 1949 ní Yâ, Arizona tí wọ́n sì pínyà ní ọdún 1950.Ní àsìkò Ogun Àgbáyé Kejì, Hailaro jẹ́ olùdarí Committee ti Negro Division ti Hollywood Victory tí òun Seye fún àwọn ológun tí wọ́n wà ní Military B.17 lobìnrin náà darapọ̀ mọ́ òṣèré Clarence múṣẹ́ tí ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ ẹgbẹ́ aláwọ̀ dúdú ti òṣèré screen Guild lati dá owó fún Red Cross fún àwọn ọmọ ilẹ̀ America ti omi yalé agbára ya Lúùkù kọlù.Ikú ReekeDaniel kú lórí àìsàn jẹjẹrẹ jẹjẹrẹ ni ọmọ ọdún 59 ní oṣù October 26 ní ọdún 1952 ní ilé ìwòsàn ti motion Picture House ní Woodland Hills, California.Ẹ̀kọ́ lósì ilé ìwé ti Denver East lati 1908 De 1910.Ipa òṣèré lobìnrin nínú eré àgbéléwòfilm film Marts Eye àti ÌdárOṣùlo Loke
wikipedia
yo
Oṣere lobinrin naa gba irawọ meji lori Hollywood Walk of Fame ti won si gba wole si awon alawo dudu ti won je osere Hall ti Fame ni odun 1975..
wikipedia
yo
hattiẹ̀ jẹ́ àkọ́kọ́ ẹni tó gba Oscar tí wọ́n fún póStage Stage ti ilẹ̀ u.S gẹ́gẹ́bí àmì igbọ́n tó wáyé ní ọdún 2006..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2010 ni wọn gba oṣere lobinrin wọle si Colorado Hall ti Fame ti Awọn obinrin.Ìtọ́kasí ẹlẹ́bùn AboDemi obinrin Oṣere Dídárajulọ 2káwọn oṣere ara Amẹrika..
wikipedia
yo
Dorothy Malone (tí a bí Mary Dorothy Láoleney; Ọjọ́ Ọkàn-din-lọ́gbọ̀n, Oṣù Kìíní, Ọdún 1924 sí ọjọ́ ọ̀kan-dín-lógún, Oṣù Kìíní, Ọdún 2018) jẹ́ òṣèré ará ilẹ̀ Amẹ́ríkà kan..
wikipedia
yo
Iṣẹ iṣe fiimu rẹ bẹrẹ ni ọdun 1943, ati ni awọn ọdun ibẹrẹ rẹ, o ṣe awọn ipa kekere, ni pataki julọ ni awọn B-Movies, pẹlu ero lati gba ipa atilẹyin ni The Big Sleep (ni ọdun 1946)..
wikipedia
yo
Lẹhin ọdun mewaa, o yi aworan rẹ pada, paapaa lẹhin ipa rẹ ni written on the wind (ni odún 1956), fun èyítí ó gba Oscar fun osere àtìlẹyìn tí ó dára jùlọ.Iṣẹ́ rẹ̀ dé ipò gíga rẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀ àwọn ọdún 1960, àti pé ó padà ṣe àṣeyọrí pẹ̀lú ipá tẹlifísàn rẹ̀ bíi Constance MacKenzie lórí péyton place (odún 1964 sí ọdún 1968)..
wikipedia
yo
Kò fi bẹ́ẹ̀ dáńgájíá tó ní eré ṣíṣe ní àwọn ọdún ìyóòkù, ìkẹhìn ìfarahàn ìbojú ìwòran tí Malone wáyé ní basic Instinct ní ọdún 1992.Malone kú ní ọjọ́ ọ̀kan-dín-lógún, oṣù kìíní, ọdún 2018..
wikipedia
yo
O ti jẹ ọkan ninu awọn irawọ ti o ku kẹhin lati Golden Age of Hollywood.ibẹrẹpẹpẹ aye rẹ won bi Malone Mary Dorothy málòney ni ọjọ okan-din-lọgbọn, Oṣu Majẹmu, ọdun 1924 ni Chicago, ọkan ninu awọn ọmọ marun-un ti Esther Emma “Iṣẹ” Smith bi ati ọkọ rẹ Robert Ignatius málòney, Olukà fun Ile-iṣẹ At&t ..
wikipedia
yo
Nigbati o jẹ ọmọ oṣu mẹfa, idile rẹ ko lọ si Dallas, Texas..
wikipedia
yo
Níbẹ ni ó ṣe àpẹẹrẹ fún Noman Marcus ó sì lọ sí Urline Academy of Dallas, Highland Park High School, Hodiphile Junior College, àti fásitì Southern Methodist tí a mọ̀ sí Southern Methodist University (JETE) lẹ́hìn náà..
wikipedia
yo
Ni akoko ti o n ṣere kan ni tòótọ́, Síkáòtù talẹnti kan Eddie Ruru ri i, ti o ti n wa lati wa oṣere ọkunrin kan.Ayé Zlone jẹ dìmọ̀kirátì, o si se ipolongo fun Adlai Ìyàwó ni akoko idibo Aare ni ọdun 1952..
wikipedia
yo
Malone, Roman Catholic kan, ṣe igbeyawo osere Jacques BerGerac ni osu kefa ojo eji-din-logbon, odun 1959, ni ile ijosin Katoliki kan ni ile Hong Kong, nibiti o wa lori ipo fun fiimu 1960 re "The Last Voyage”
wikipedia
yo
Wọ́n ní ọmọbìnrin méjì, Mími (tí a bí ní ọdún 1960) àti Diane (tí a bí ní ọdún 1962), kí wọ́n tó wá kó ara wọn sílẹ̀ ní oṣù kejìlá, ọjọ́ kẹjọ, ọdún 1964.Malone lẹ́hìn náà ṣe ìgbéyàwó sí oníṣòwò àti alágbàtà New York kan, Robert tokin ní oṣù kẹrin ọjọ́ kẹta, ọdún 1969, ní Silver Bells Wedding Chapel ní Las Vegas, Nevada..
wikipedia
yo
Igbeyawo keji re ti wa fagile lehin ti Malone so pe toMarkin fe oun nitori owo re.lone se igbeyawo si olori Dallas Motel chain, Charles Huston Bell ni osu Kẹwàá ojo keji, odun 1971, won si ko ara won sile lehin odun meta.Ni nǹkan bi odun 1971, Malone gbe awon ọmọbinrin re lati Southern California lo si ṣuburban Dallas, ni Texas, nibiti o ti dagba.Awon itọka si..
wikipedia
yo
Monica Imes (Ọjọ́ìbí December 11, 1967), To gbajúmọ̀ bí Mo'que, jẹ́ aláwàdà àti òṣèré lobinrin ara Amẹ́ríkà tó gba Ẹ̀bùn Adèmí bí obìnrin osere kejì dídárajulojulọ.Ìgbésí ayé Arábìnrin náàmo'que ni a bini Woodlawn, Baltimore County ní Maryland..
wikipedia
yo
Òṣèré lobìnrin náà jẹ́ ọmọ Alice Imes (Brasil) àti Steven Imes (olùbádámọ̀ràn ti Ogun)..
wikipedia
yo
Ki Mo'nique to di osere lobinrin ni o sise gegebi Mèsáyà Service Representative ni ilé ise Ero ìmúlẹwọ Mci ni hunt Valley, Maryland..
wikipedia
yo
Òṣèré lobìnrin náà fẹ́ Mark Jackson ní ọdún 1991 di 2001 tí wọ́n sì bí ọmọ ọkùnrin méjì; Mark Eric Jackson Jr..
wikipedia
yo
Mo'queque bi ibeji okunrin meji Jonathan ati David Hicks ni osu October odun 2005 fun Sidney Hicks ti won si fe ara won ni odun 2006.Eko'Niqueque jade ni Milford Mill High School ni ilu Baltimore County ni odun 1985 ati ile iwe giga ti Morgan..
wikipedia
yo
Ni a bini ọjọ kọkanla oṣu December ni ọdun 1931 ti osijẹ onijo, akọrin ati oṣere..
wikipedia
yo
Rita gba ẹ̀bùn Adèmí bi obinrin òṣèré keji dídárajulọ.Ìgbésí ayé arabinrin naaabi Rita si Humacao, Puerto Rico fun Rosa Maria (olùràn aṣọ lobinrin) ati Francisco Jose (agbe)..
wikipedia
yo
Moreno bẹrẹ si ni ko ijo akọkọ lati owo onijo ile Spanish ti orukọ rẹ nje Paco cansino..
wikipedia
yo
Oṣere lobinrin naa ko ipa rẹ Broadway akọkọ gegebi itan ninu skydt nigba ti o wa ni ọmọ ọdun mẹtala..
wikipedia
yo
Ìrìn Àjò Moreno lórí eré àgbéléwò bẹ̀rẹ̀ ní ọdún tó padà pé ti Golden Age ti Hollywood.Láti ọdún 1954 títí dé ọdún 1962, Moreno wa ní ipasẹ̀pọ̀ tí ó ṣe bẹ́ domọ́rán pẹ̀lú kẹ̀un Brandon níbi tí ó ti lóyún fún ṣùgbọ́n ọmọ náà padà kú sínú oyún nígbà tí ó fẹ́ yọ dànù.Ní ọdún 1965, Moreno fẹ́ Dókítà Olúwọ̀ ọ̀kan Leonard Gordon tí ó sì di manager fún òṣèré lobìnrin náà lẹ́yìn tí ó fẹ̀yìntì ní ìdí iṣẹ́ ìṣègùn..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1995, ọkọ àti ìyàwó náà kó lọ sí Berkeley ní California níbi tí wọ́n sì ti wà papọ̀ títí Leonard fi kú ní ọdún 2010..
wikipedia
yo
Moreno ati Gordon bí ọmọ obinrin kan Fernanda Gordon Fisher tí ó síbi ọmọ meji lọkunrin.Àmì ẹ̀yẹ àti ìdánilémore gba àmì ẹ̀yẹ ti Emmy, Grammy, Oscar àti Tony..
wikipedia
yo
Òṣèré lobìnrin náà jẹ́ ọ̀kan lára àwọn mẹ́rin lẹ́elogún tí wọ́n fi jẹ́ triple crown of Acting..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2004, Rita gba Medal òmìnira ti are orílẹ̀ ède láti ọ̀dọ George W.bush ti ilẹ̀ America..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2009, are Barack Obama fún osere náà ní Medal Arts ti National.Ní ọdún 2015, òṣèré lobinrin náà gba àmì ẹ̀yẹ ti Kennedy Center Honor fún ipa rẹ̀ nínu gbígbé àṣà ilẹ̀ America lárugẹ pẹ̀lú eré orítage..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2019, Rita gba àmì ẹ̀yẹ ti Peabody.Ìtọ́kasí ẹlẹ́bùn Aakadèmí obìnrin òṣèré didarajulọ 2k..
wikipedia
yo
Jẹ́ Olùkọ̀wé àti Òṣèré lobinrin ilẹ̀ America tí a bini ọjọ́ karùn oṣù November ní ọdún 1963.Ìgbésí ayé arábìnrin náàtatum ni wọ́n Bísí Los Angeles, California fún òṣèré Ryan O’Wíkun àti Joanna Moore..
wikipedia
yo
Iya Tatum kú ní ọmọọdún mẹ́ta lélọ́gọ́ta lórí àrùn jẹjẹrẹ ti Lunda.Ní ọdún 2021, O'Wíki kópa nínú fíú “Máṣe gbàgbé” tó dálórí ìdáni kọ́kọ́ àti ìkọ́ owó jọ láti jà fún àìsàn Alzheimer.filmṣoṣober Eye ẹ̀yẹ àti látab jẹ́ ọ̀dọ̀ tó kéré jùlọ láti pegedé nínú ìdíje àmì ẹ̀yẹ Adèmí ní ọmọ ọdún mẹ́wá níbi tí ó ti ṣeré gẹ́gẹ́bí addíẹ̀ Logins nínú eré Paper Moon ní ọdún 1973..
wikipedia
yo
Ni odun 1974,ta gba ami eye AkaDemi gegebi Oluráranilowo osere lobinrin to dara jù.Ìtọ́kasíàwọn ẹlẹ́bùn AboDemi Obìnrin Òṣèré Dídárajùlọ 2K..
wikipedia
yo
Tí wọ́n bí ní ọjọ́ ìwònlélógún Oṣù keje, ọdún 1982) jẹ́ òṣèrébìnrin orílẹ̀-èdè New Zealand tó gba ẹ̀bùn ADemi obinrin òṣèré kejì didarajulo.Igba Ewe ati bi o se kẹ́kọ̀ọ́won bí Anna paquin sí Winnipeg, Manitoba, o je omoMary paquin (NE Bromeke) ati Brian PAquin.PAquin lo si ile eko alako Rphapha House House Steiner School kí o tó tẹ̀síwájú ló kó hutt Interte School (1994-95), ti o si lo ile-iwe girama ti Wellington Girls' College, o gba re iwe-ẹri girama ní Windward School in ilu Los Angeles.Àwọn fíìmù tí ó ti kópa àwon ẹlẹ́bùn akanu obinrin osere didara 2
wikipedia
yo
Ni a bini osu November, ọdun 1927 to je osere lobinrin, olorin ati oludari ti Stage.Ìgbésí ayé arabinrin náàEstelle ni a Bísí ilé ìwòsàn ti Lynn..
wikipedia
yo
Ìyá òṣèré lobìnrin náà Elinor Ingeborg tí a bini ilẹ̀ Sweden àti bàbá rẹ̀ ẹ̀ben Parsons tó wá láti ìran èdè Gẹ̀ẹ́sì.Parsons fẹ́ olùkọ́ ìwé Richard Gehman ní ọdún 1953 tí wọ́n sì bí ìbejì lobìnrin Abbie (oluka) àti Martha gehman (òṣèré lobìnrin)..
wikipedia
yo
Tọ́kọ taya náà pínyà ní ọdún 1958.Ní oṣù January, ọdún 1983, Estelle fẹ́ Peter Zìjọbaràpadà tí wọ́n sì gba ọmọ ọkùnrin kan tó tórúkọ Ren jẹ́ Abraham..
wikipedia
yo
Zìjọba kú ní ọjọ́ kẹjọ oṣù November ní ọdún 2021.Nepalọ LoBirta náà losi ilé ìwé ti oak grove fún àwọn obìnrin ní Maine..
wikipedia
yo
Estelle náà jáde láti Collegi ti Connecticut ní ọdún 1949 lẹ́yìn náà lọ lósì ilé ìwé gíga ti Boston láti kéÈkó lórí amòfin.Àmì ẹ̀yẹ at AcplaeỌ̀pọ̀lọpọ̀ gba ẹ̀bùn Adèmí bí obìnrin òṣèré kejì dídárajùlọ tí wọ́n tún yàn fún àmì ẹ̀yẹ Tony lẹ́ẹ̀mẹ́rin..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2004, òṣèré lóbìnrin náà ni wọ́n gbà sí Theatre Hall ti Fame ti ilẹ̀ America.Ìtọ́kasí ẹlẹ́bùn AboDemi obìnrin òṣèré didarajulọ 2K..
wikipedia
yo
jẹ́ òṣèrébìnrin tó gba ẹ̀bùn ADemi bi obìnrin òṣèré kejì dídára.Ìtọ́kasí.Àwọn ẹlẹ́bùn ADemi obìnrin òṣèré dídára 2K..
wikipedia
yo
Je ọmọ osere lọkunrin sir Michael Reve ati oṣere lobinrin Rachel Kempson ti a bini ojo ogbon osu January ni odun 1937..
wikipedia
yo
Arabinrin naa jẹ oṣere to gba ẹbun Adèmí bi obinrin oṣere keji didarajulọ.igbesi aye arabinrin naaVanessa keko ni ile iwe Tadale fun awon omo obinrin; ile eko Alice Ottley ni Worcester ati ile eko Queen's Gate.Vanessa wo ile iwe siso ọrọ ati Drama ni ọdun 1954..
wikipedia
yo
Òṣèré lobìnrin náà kọ́kọ́ jáde sí ojú eré West End fún ìgbà àkọ́kọ́ ní ní ọdún 1958..
wikipedia
yo
Oṣere naa fẹ adari ere Tony Richardson lati 1962 ti wọn si bi ọmọbinrin meji; Natasha ati Joely to di oṣere lobinrin..
wikipedia
yo
Vanessa ati Ruchard pínyà ní ọdún 1967.Ami ẹ̀yẹ àti ìdáni lọ́láVanessa gba àmì ẹ̀yẹ Telivision Academy ti British, àmì ẹ̀yẹ Golden Globe àti àmì ẹ̀yẹ méjì ti Primetime Emmy.Ìtọ́kasí.Àwọn ẹlẹ́bùn Adèmí obìnrin òṣèré didarajulọ 2K..
wikipedia
yo
Donna Reed (wọ́n bi ​ Belto Mullenger; ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kìíní , ọdún 1921 – ó sì fi ayé sílẹ̀ ní ọjọ́ kẹrìnlá, oṣù kìíní, ọdún 1986) ó jẹ́ òṣèré Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Ìgbà tó fi ṣe eré lọ fún bíi ogójì , pẹ̀lú àwọn ipa àti akitiyan rẹ̀ ní fíìmù tó ju ogójì lọ..
wikipedia
yo
Àwọn ènìyàn mọ̀ ó dáadáa fún ipá rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Mary Hch Bailey ní eré Frank Capra tó pè ní Fantasy káwọn film It's a wonderful Life (1946)..
wikipedia
yo
Reed gba Academy Award for Best Supporting Actress fun Fred Znemann's War Fiimu From Here to eterÌṣàkóso (1953).ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ Aye rẹ̀ won bi Reed si Donna Belle Mullenger ni ọkọ lẹ́ẹ̀gbẹ̀ Chson, Iowa, ó jẹ́ ọmọbìnrin fún Hazel Jane (ti ọ̀pọ̀ ènìyàn mọ̀ sí Shives) àti William Richard Mullenger..
wikipedia
yo
Oun lo dagba ju láàárín àwọn ọmọ márùn-ún tí àwọn òbí ẹ̀ bí, wọ́n tọ́ dàgbà bíi Mdísì..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1936, nígbà tó wà ní kíwágbò tó kàn kó tó parí ìwé-ilé rẹ̀ ní Dson (Iowa) , Kemisitiri tíṣà rẹ̀ fún un ní How to win Friends and influence People..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tó kà á tán, ó gba òṣèré àkọ́kọ́ ní ẹrẹ̀ tó ṣe ní ilé-ìwé rẹ̀, wọ́n tún dìbò fún un ní ilé-ìwé rẹ̀ fún olórí wọn àti wí pé ó wà ní àwọn mẹ́wàá àkọ́kọ́ tó ṣe tán ní ọdún 1938 ní ilé-ìwé náà..
wikipedia
yo
Tompkins bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣiṣẹ́ lórí Manhattan project.Lẹ́yìn tó parí ìwé ẹ̀ tán-ná ni Døjer, Reed lérò láti di olùkọ́ ṣùgbọ́n kò rówó san fún Fáàmì..
wikipedia
yo
Nígbà náà ló padà lọ sí Kalifonai tó lọ sí ilé-ìwé Los Angeles City College ní ìmọ̀ Aanti rẹ̀..
wikipedia
yo
Nígbà tó wà ní Fásitì, ó ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré orí-ìtàgé, àmọ́ nígbà náà kò tí ì ní lọ́kàn láti di òṣèré..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí ọ̀pọ̀ àwọn pé ẹ tó darapọ̀ mọ́ àwọn ni ó padà darapọ̀ mọ́ screen test ní situdi wọn, Reed tọwọ́ bọ̀wé pẹ̀lú Metro-goldwyn-Mayer; lẹ́yìn ìgbà náà, a pinnu láti parí ẹ̀kọ́ rẹ̀ tán náà..
wikipedia
yo
Ó parí ẹ̀kọ́ Fásitì rẹ̀, lẹ́yìn náà ló tọwọ́ bọ̀wé pẹ̀lú ilé-iṣẹ́ Agent.Òfì Àwọn Akun àti àwọn ibi tó wọ́n ti yanno fún àwọjipọ̀ àwọn ẹlẹ́bùn Adèmí obìnrin Òṣèré dídárajùlọ 2k..
wikipedia
yo
Anne Revere (Osu kefa, ojo marun-un-din-lọgbọn-lọgbọn, ọdun 1903 si osu kejila ojo meji-din-logun, ọdun 1990) je oṣere ara ile Amẹrika ati ọmọ ẹgbẹ ti n lọ siwaju ninu Igbimọ ti screen Actor's Guild..
wikipedia
yo
O je gbajumo fun ise re lori Broadway ati awon ipa re bi iya ninu awon ere osere lẹsẹsẹ to ni iyi..
wikipedia
yo
Revere gba Ààmì Ẹ̀yẹ ADemi fún ipa àtìlẹyìn rẹ̀ nínú fiimu National Inst (ọdún 1945)..
wikipedia
yo
Wọ́n sì yàn án ní ẹ̀ka kan náà fún “The Song of Bernadette” (ní ọdún 1943) àti Gentleman's agreement (ní ọdún 1947)..
wikipedia
yo
O gba awoòdú Tony fun ise re ninu Lilian Hellman's play Toys in the Attic ni odun 1960.ibẹrẹ Aye rea bíi ni Ile New York, Revere je omo taara ti akoni iyika Amerika Paul Revere..
wikipedia
yo
Bàbá rẹ, Clinton, jẹ́ alágbàáta ọjà, àti pé ó dàgbà ni Upper West Side àti ní Westfield, New Jersey..
wikipedia
yo
láìbìkítà àwọn ìgbìyànjú rẹ̀ tí kò ní àṣeyọrí láti darapọ̀ mọ́ àwọn ẹgbẹ́ ìyàlẹ́nu ní ilé-ìwé gíga àti (ní ìbẹ̀rẹ̀) Kọ́lẹ́ẹ̀jì, ó padà ṣe àṣeyọrí ní WelLesley tí ó sì kọ́ ẹ̀kọ́ ẹrẹ̀ ṣiṣẹ́ ìyàlẹ́nu níbẹ̀..
wikipedia
yo
ó tẹ̀síwájú láti f'orúkọ sílẹ̀ ní ilé-ìwé American Laboratory School láti kó eré ṣíṣe pẹ̀lú Maria ous:káyà àti Richard Bolesmọ́mìsky.Àwọn ìtọ́ka sí..
wikipedia
yo
Ni a bini ojo keji dinlogbon osu February ni odun 1948 je osere lobinrin to gba ebun ADemi bi obinrin osere keji didarajulọ.Ìgbésí ayé arabinrin Naarue ni a Bisi Jackson Heights, Queens, New York City fun Mercedes J..
wikipedia
yo
Baba osere lobinrin naa wa lati iran German ati Irish, iya rẹ wa lati iran Cuban ati Irish..
wikipedia
yo
ruehl ni ó dàgbà sí ìlànà Catholic.Òṣèré kòbìnrin naa bẹrẹ irin ajo iṣe rẹ̀ ni Theatre pẹ̀lú ilé iṣẹ́ Denver Center Theatre.Ni ọdún 1999, rue fẹ́ David Gjakini tí ó jẹ́ Paka..
wikipedia
yo
Oṣere gba ọmọ ọkunrin kan to ti orukọ rẹ nje jake ti a bini ọdun 1995..
wikipedia
yo
David G.: ku lójijì ninu orun re ni ile re ni ojo kerin dinlogun osu October ni odun 2020 lori aisan okan.Ekorue losi Collegi ti New Rochelle ti o si kawe ja pelu ba lori ede Geesi ni odun 1969.Ami eye ati gbélẹ̀tọ́kasíàwọn ẹlẹ́bùn AyORIU obinrin osere didarajulo 2K..
wikipedia
yo
dame Margaret Taylor Rutherford,(dbe) ni wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlá oṣù kaàrún ọdún 1892 , tí ó sì dágbére fáyé ní ọjọ́ kejìilélógun, oṣù karun, ọdún 1972..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ òṣèrébìnrin tó gba ẹ̀bùn ADemi tí obìnrin òṣèré kejì dídára nígbà àyè rẹ̀.Ó di gbajúgbajà lẹ́yìn ìjà Ogun Àgbáyé Tuntunth Farav. Fíìmù tí ó ti kópaàwọn ẹlẹ́bùn Abọ̀wọ̀ obìnrin òṣèré dídára 2K..
wikipedia
yo
Eva Marie Saint (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrin oṣù kẹfà, ọdún1924 ) jẹ́ òṣèré fíìmù Amẹ́ríkà, tíátà àti tẹ̀léfíson..
wikipedia
yo
Ni fun igba to ju ogoje odun lo, o gba awoOdu Adèmí ati Primetime Emmy Award, pẹlu yiyan fun Golden Globe Award ati British Academy Film Awards lẹẹmeji..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ikú Olivia De AtVilland ní ọdún 2020, Saint di òṣèré tó dàgbà jù tó ti gba àwọọdú Adèmí àti òṣèré tó ṣẹ́kù láyè lára àwọn òṣèré tó gbajúmọ̀ nínú sinimá Golden Age of Hollywood.Wọ́n bí sí New Jersey, ó dàgbà sí New York, Saint lọ sí Bowling Green State University àti wí pé ó bẹ̀rẹ̀ ìrìnàjò ayé rẹ̀ pẹ̀lú òṣèré tẹ́lẹ̀físon àti rédíò ní 1940s..
wikipedia
yo
O lo si Bethlehem Central High School ni DelMar, New York, lẹ́gbẹ̀ẹ́ Albany, ó ṣe tán ní ọdún 1942..
wikipedia
yo
O di ara Hall of Fame Ile-iwe sekondiri ni ọdun 2006..
wikipedia
yo
O ko imo osere sise ni Bowling green State University ati darapo mo Delta gamma sorodraising..
wikipedia
yo
Ní àsìkò yìí, ó ṣe olórí òṣèré ni Personal appearance..
wikipedia
yo
Tíátà tó ṣe ní ọgbà Bowling Green tó padà sọ lẹ́yìn rẹ̀..
wikipedia
yo
Ó jẹ lára àwọn ẹgbẹ́ tíátà ọlọ́lá tó kó ara wọn jọ bíi ọmọ-ìyá, Theta Alpha phi,àti wí pé òun ni ó ń tojú rẹ̀kòdù fún àwọn àjọ ọmọ-ilé ìwé ní ọdún 19...
wikipedia
yo
4Àwọn fíìmù Maria Ìtọ́kasí àwọn ẹlẹ́bùn ADemi obìnrin osere didarajulọ 2k..
wikipedia
yo
jẹ́ òsèré lóbìnrin ilẹ̀ America tí a Bìní Oṣù Febuary, Ọdún 1899 tó sì kú ní Oṣù August, Ọdún 1985.Ìgbésí ayé arábìnrin náà ní Níbìnrin náà ní A Bisi ìlú Litch, Minnesota fún Hans Sonder àti Anna Kirstine Sonder.Engaard Ogaard fẹ́ òṣèré Neill O'Malley ní ọdún 1922 tí wọ́n sì pínyà ní ọdún 1930..
wikipedia
yo
Ni osu May ni odun 1930, osere binrin naa fe Herbert biberman ni ilu Philadelphia, Pennsylvania..
wikipedia
yo
Toko taya náà gba àwọn ọmọ méjì tó (Joan Kristine biberman àti Daniel Hans biberman).Lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ àìsàn rọ́pá Rose, Sonder kú sí ilé ìwòsàn ti motion Picture àti Television ní ìlú Woodland Hills, California ní ọdún 1985 lórí àìsàn tí àwọn Òyìnbó pè ní Vascular Thrombọ́sí.Ẹ̀kọ́ tọ́kasí ṣiṣẹ́ ní ilé ìwé gíga ti Minnesota níbi tí òṣèré lóbìnrin náà ti jẹ́ ẹ̀kọ́ ti ìmọ̀ eré ìtàgé.Àmì ẹ̀yẹ àti ìdániọ̀ló lobìnrin náà gba ẹ̀bùn Adèmí bí obìnrin òṣèré tó ranilọ́wọ́ kejì dídára.Ìtọ́kasí àwọn ẹlẹ́bùn Adèmí obìnrin obìnrin dídára 2 2k..
wikipedia
yo
Mira Katherine Sorìsìnkú (; wọ́n bí ní ọjọ́ crin oṣù kẹsan-an, ọdún 1967) jẹ́ òṣèré Amẹrika..
wikipedia
yo
Ó gba awoọdú Adèmí àti Golden Globe fún òṣèré tó ṣẹ́gi lẹ́yìn ọgbà fún ipa rẹ̀ ní eré Kíkà Allen tó pè ní Mighty Aphrodite (1995).Orúkọ rẹ̀ wà lára àwọn orúkọ àkọ́kọ́ tó bẹ̀rẹ̀ àwọn fíìmù bíi My and Michèle's High School Réunion (1997), ẹ̀wùgi (1997), lùlù on the bridge (1998), the Ibùdóment Killers (1998), Summer of Sam (1999), and Like Dandécted dust (2009)..
wikipedia
yo
Fún àwọn ìṣe rẹ̀ lórí tẹ̀léfínnn, wọ́n yànhò fún àwọn àwoOdu bíi Primetime Emmy Award for Ọkùnrin Lead Actress in a limited series or movie fún ipa tó kó gẹ́gẹ́ bí Marilyn Mone ni Norma Jean & Marilyn (1996), àti wí pé wọ́n yanhò lẹ́ẹ̀mejì fún Golden Globe for Best Actress – miniseries or Television Film, bákan náà fún ipa tó kó gẹ́gẹ́ bí Marilyn Mone àti ipa tó kó gẹ́gẹ́ bí olórí òṣèré ní Human Trafficking (2005).ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bi Sorìsìnkú ní Manhattan, New York City sí ilé Lorraine Ruth Davis, tó jẹ́ òṣèré tẹ́lẹ̀ rí ; àti Paul Sor!’ òṣèré, òṣèré àti olùdarí..
wikipedia
yo
Orisun rẹ jẹ lati ara ìtíli lati ọdọ baba .Won to ni teNAAAAly, New Jersey, nibi to ti ko ati ṣere èyìnle fun ọrẹ rẹ lati kekere Hope Davis, ni Tiata Dwight-engwood School.Fiimu:Nitoent awọn ẹlẹ́bùn Arindèmí obinrin obinrin didarajulọ 2K..
wikipedia
yo
Lois Maureen Stapleton jẹ́ òṣèré sinimá àgbéléwò tó gba àmìn ẹ̀yẹ Adèmí gẹ́gẹ́ bí òṣèrébìnrin àṣegbé fún olú ẹ̀dá ìtàn tó dára jù lọ.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ètò ẹ̀kọ́ kòpọ̀ bi Stapleton sí Troy, New York,tí àwọn òbí rẹ̀ jẹ́ John p..
wikipedia
yo
Stapleton ati Irene (née Walsh).itọkasi awon ẹlẹ́bùn ADemi obinrin osere didarajulọ 2K..
wikipedia
yo
Tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kejì Oṣù kẹjo ọdún 1953 jẹ́ òṣèrébìnrin, Alawaada,olórin orílẹ̀ èdè America tó gba ẹbùn ARInu ti obìnrin òṣèré kejì didarajulo.ibẹrẹ AyeENI rẹ̀ Steen| ni wọ́n bí ní Ọjọ́ kejì Oṣù kẹjo ọdún 1953 sí Newport, iṣẹ́ sí ìdílé Nellie Mae (née Wall) ati Maurice Hoffman Steja-ní ọdún 1971, ó bẹ̀rẹ̀ sí keeko ní Henedxx College tí ó ti kọ́ nípa eré orí ìtàgé.Àwọn eré tí ó ti kópamáwòrán àwọn ebun ati amì àwọn ìtọ́kasí̀ji àwọn ẹlẹ́bùn akanu obinrin osere didara 2..
wikipedia
yo
Beatrice Whitney straight (tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kejì Oṣù Kẹjọ Ọdún 1914, tí ó sin kú ní ọjọ́ keje Oṣù Kẹrin ọdún 2001), nígbà ayé rẹ̀ jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò, àti gbajúmọ̀ nínu ẹbí Whitney ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
O ti gba amin ẹyẹ Academy Award, amin ẹyẹ Tony ati adije amin ẹyẹ Emmy.Àtẹ Àtòjọ diẹ ninu awọn sinima-àgbéléwò rẹ-àgbéléwò-ìrìnnàtẹlifíṣọ̀n àwọn Jũ àwọn ẹlẹ́bùn obìnrin Òṣèré dídára 2
wikipedia
yo
jẹ́ òṣèré lóbìnrin ti ilé British òṣèré tó gba ẹ̀bùn Adèmí bi obinrin òṣèré keji dídárajulọ.Ìgbésí ayé Arábìnrin náàKatherine Matilda Swinton ni a bi ni ọjọ́ karun osu November ọdún 1960 si ìlú London fun Judith BalFour (1929-2012) ati sir John Swinton (1925-2018)..
wikipedia
yo
Baba osere lobinrin naa je osise feyinti Major-General ti ologun ile ati oga Lieutenant ti BerWick (1989-2000), Iya re si je omo ile Australia.Ni odun 1997, Tilda bi ibeji Honor ati Xavier Swinton Byrne fun John Byrne ti o si gbe Scotland fun ogun odun..
wikipedia
yo
Oṣere lobinrin naa bẹrẹ ere Oritage lati igba ti o ti wa ni ile iwe..
wikipedia
yo
Swinton lo odun meji gegebi eni Jọ̀wọ́ ara re sile lati se iranlọwọ ofe ni ile South Africa ati Kenya ki o to lo si ile iwe giga ti Cambridge.Eko ↑ losi ile eko Queen's Gate, ile eko awon ọdọmọbinrin eto ilera West ati ferat College fun igba die.Ni odun 1983, Swinton kawe yege ni ile iwe giga ti Cambridge lori imo Social ati Science ti oselu.Ami eye ati yínKùagboun gba ami eye Akadèmí, Ami eye BAFTA ati Ami eye independent Spirit..
wikipedia
yo