cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Theatre ti Ethel Barrymore ní aso lórúkọ òṣèré lobinrin náà ní New York City.EkoEthel dàgbà sí ìlú Philadelphia níbi tó ti lọ sí ilé ìwé ti Roman Catholic.Ami Eye àti ìdaBarrymore gba irawo kan lori Hollywood Walk of Fame lẹ́yìn ikú rẹ̀ lórí akitiyan rẹ̀ nínu eré Oritage ní ọdún 1960.Òṣèré lobinrin náà gba ẹ̀bùn ADemi bi obìnrin osere tó ranilowo kejì dídáraga.Ìtọ́kasí àwọn ẹlẹ́bùn Adèmí Obinrin obìnrin didara 2 2..
wikipedia
yo
jẹ́ òṣèré tó gba Ẹ̀bùn Adèmí bí obìnrin òṣèré kejì dídárajùlọ.Ìgbésí ayé arábìnrin náàbásinger ni a bini Athens, Georgia ní ọdún 1953 fún an Lee (1925-2017) àti Donald Wade (1923-2016).singer jẹ́ alumna tí William Esperper Studio fún performing arts ní Manhattan, New York City.Kí òṣèré lobìnrin náà tó gbajúmọ̀ ni ó fẹ́ Tim Sacasal, Dale Robinette àti Joe Selth.Ní oṣù October, ọdún 1980, Kim fẹ́ Ron Syd-g8C tí wọ́n sì pínyà ní ọdún 1989.Ní ọdún 1990, Kim pàdé ọkọ rẹ̀ kejì Aleday baldwin tí wọ́n sì fẹ́ ara wọn ní Oṣù August ní ọdún 1993 tí wọ́n sì bí ọmọ obìnrin Ireland EliEsse baldwin tí wọ́n bí ní Oṣù October, ọdún 1995..
wikipedia
yo
tọkọ taya náà pinya ní ọdún 2002.Ní ọdún 2014, Kim fẹ́ Mitch stone tí wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí ní gbé pọ̀ láti ìgbà náà.Ẹ̀kọ́-singer keko nípa Ballet láti ọmọ ọdún mẹ́ta..
wikipedia
yo
Oṣere lobinrin naa keko ni ile iwe giga Georgia.ami eye ati ìdakim gba ami eye ti ADemi, Ami Ẹyẹ ti Golden Globe, Ami Eye ti Oṣere Screen Gujàgídíjàgan ati irawo ti Hollywood walk of Fame.Ìtọ́kasí.Àwọn ẹlẹ́bùn ADemi obinrin osere didarajulọ 2k..
wikipedia
yo
Ni wọ́n bí ní ọjọ́ keje Oṣù Kaàrún Ọdún 1923 , tí ó sì dágbére Faye ní ọjọ́ kejìila, Oṣù Kejìila, Ọdún 1985..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ òṣèrébìnrin tó gba ẹ̀bùn ADemi tí obìnrin òṣèré kejì dídára nígbà ayé rẹ̀.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀anne Baxter ni wọ́n bí ní ọjọ́ keje, Oṣù Kaàrún Ọdún 1923 ní ìlú Michigan, Indiana sí ìdílé Catherine Dorothy (Nee Wright; 1894-1979)..
wikipedia
yo
òlùlù WestChester County, New York ni won ti wo dagba.Awon ebun ati ami eyejiji ẹlẹ́bùn Adèmí obinrin osere didarajulọ 2K..
wikipedia
yo
Juliette Binche (; tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹ̀sán-án Oṣù Kẹta, Ọdún 1964) jẹ́ òsèré àti oníjó Faransé..
wikipedia
yo
O se afihan ni fiimu bii ọgọta ti wọn pe e si ati wi pe o tun jẹ ẹni to gba awon awoọdú bii awoọdú ADemi, British Academy Film Award, Silver Beikun, Cannes Film Festival Award, Vol, Volpi Cup ati CésarBinche bẹ̀rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí ní ma kọ́ bi wọ́n ṣe maa n se eré ní Odò ..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré tó ṣe lórí ìtàgé, orúkọ rẹ̀ wà nínú fiimu tí gbogbo ènìyàn mọ Siçur tí Jean-Luc Gojoró jẹ́ atọ́kùn rẹ̀ (hail Mary, 1985), Jacques Doillon (Family Life, 1985), àti André Seter, tí eré ìgbẹ̀yìn yìí jẹ́ kó di gbajúgbajà ní Faransé tí ó fi jẹ́ kí ó di olórí òṣèré ní eré oníṣe Renndez-vous (1985)..
wikipedia
yo
Eré àkọ́kọ́ tó jẹ́ ti gẹ̀ẹ́sì tó ṣe the Unbearable lightness of Being (1988), tí eré yìí jẹ́ kó di ènìyàn ti àwọn ènìyàn púpọ̀ wá mọ́..
wikipedia
yo
Nigba odun 2000, o ti wa nipo ẹni to ti ṣe aṣeyọri ti ko de fẹ ko bo..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2010, ó gba àrùọdú fún òsèré tó dára jùlọ níọdún ní Cannes Film Film Festival fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Abbas Kistami ní eré tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ cerble copy copy..
wikipedia
yo
Wọ́n tún fun ní àwọ̀òdú Maureen O'Hara Award ni Kerry Film Festival ní ọdún 2010, Awost tó jẹ́ wí pé obìnrin tó bá ṣe àṣeyọrí ni iṣẹ́ òṣèré nìkan ló ma fun .Àwọn eré rẹàwọn ìtọ́kasí àwọn ẹlẹ́bùn Adèmí obìnrin òṣèré dídárajùlọ 2K..
wikipedia
yo
jẹ osere to gba ebun ADemi bi obinrin osere keji didarajulọ.Ìtọ́kasíàwọn ẹlẹ́bùn AboDemi obìnrin Òṣèré didarajùlọ 2k..
wikipedia
yo
Alice Brady (orukọ àbísọ rẹ̀ ni Mary Rose Brady; Ojo ibi jẹ́ November 2, 1892 sí October 28, 1939) jẹ́ òṣèré kan ní Orílẹ̀ Èdè Amẹ́ríkà ti í bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ náà ní àkókò tí wọ́n ń pè ní Silent era, èyí tí ó padà di àsìkò tí wọ́n pè ní Sound film/tal..
wikipedia
yo
Ó ṣiṣẹ́ títí di oṣù mẹ́fà kí ó padúnu ẹ̀mí rẹ̀ sórí ààrùn jẹjẹrẹ cancer ní ọdún 1939..
wikipedia
yo
Awon ere fiimu re naa ni; My Man Godfrey ni 1936, ninu re ni o ti sere gege bi carole LoAMWDI ati ninu fiimu "in Old Chicago ni odun 1937 eyi ti i gba ami w AkaDemi fun Best Supporting Actress.Ni odun 1960, awon oruko fun ami eye Hollywood Walk of Fame Motion Pictures, eyi ti oruko re naa wa lara won fun awon ohun ti o ti se afikun afikun ninu ise ere sise..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ òṣèré tó gba àmì ẹ̀yẹ Adèmí bi obìnrin òṣèré kejì tí ó dídárajùlọ.ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayéMary Rose Brady jẹ́ ẹni tí wọ́n bí sí ìlú NewYork..
wikipedia
yo
Iya re, osere Faransee, ti oruko re n je Rose Marie rene jade laye ni odun 1896Rose Brady je eni ti o nifee si ere sise lati igba ewe..
wikipedia
yo
Ó sì kọ́kọ́ wo ìtàgé nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹ́rìnlá, ó sì gba iṣẹ́ àkọ́kọ́ rẹ̀ sí Broadway Theatre ní ọdún 1911 nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún méjìdínlógún èyí tí bàbá rẹ̀ náà kópa nínu eré náà.Iṣẹ́ tí ó yàn ní B==Mary Rose Brady kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ìtàgé ṣíṣe ní 1911 ní New Haiven nínu eré òpereta tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "The Balkan Princess ..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1913, Brady kópa nínu “A thief thief for a Night" pẹ̀lú John Barrymore ti P.G wọ́dehouse ko ati John Stapleton ko gege bi itan novel, ati a Gentleman of leisure ni ile ìwòran Theatre ti McVicker ní ìlú Chicago..
wikipedia
yo
Ó tẹ̀síwájú láti tún ṣeré ṣùgbọ́n nínú àwọn ère tí baba rẹ̀ ṣe títí ó fi pé ọmọ ọdún méjìlélógún..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1931, óo wà ninu àfihàn eré tí àkọlé rẹ̀ ń jẹ́ mourning becomes electral láti ọwọ́ Eugene O'Neill..
wikipedia
yo
Ìyàwó baba rẹ̀ tí í ṣe Grace George tí bàbá rẹ̀ fẹ́ nígbà tí Alice wà ní kékeré bí ọmọ ọkùnrin tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ William A..
wikipedia
yo
Brady's father moved into movie production and wẹkutation in 1913, with his world film company, and Brady soon followed along after him, making her first silent Àpapọ̀re appearance in as yé Sow in 1914..
wikipedia
yo
She appeared in 53 films in the next 10 years, all while continuing to perform on Stage, the film Industry at the time being centered in New York..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1923, óo dẹ́kun láti má ṣe eré fiimu àgbéléwò, èyí tí ó wá bọ́sí orí kí a má ṣe eré orí ìtàgé, èyí tí kò sì ṣe tí ti di ọdún 1933, nígbà náà ni ó wá lọ sí Hollywood in 1923, she Stopped appearing in films to concentrate on Stage Acting, and did not appear on the screen Again until 1933, when she made the Move to Hollywood lẹ́yìn èyí ni ó kópa nínú “When Ladies Meet ní ọdún 1933” , èyí jẹ́ eré àkọ́kọ́ tí yóò jẹ́ Sound film àti kí a ma ya fọ́tò..
wikipedia
yo
Ati ìgbá náà ni ó ti ń ṣiṣẹ́ takuntakun títí ó fi jáde láyé, àwọn eré tí ó ti ṣe náà jẹ́ márùndínlọ́gbọ̀n tí ó ṣe nínú ọdún méje..
wikipedia
yo
Lincoln' ní ọdún 1939.Ìgbé ayé àti ìgbẹ̀yìn ayébrady fẹ́ òṣèré tí ó ń jẹ́ James Crane CranEll láti ọdún 1919 dé 1922 èyí tí ó jẹ́ ọdún tí wọ́n kọ r'Awon sile..
wikipedia
yo
Àwọn méjèèjì bí ọmọ ọkùnrin kan tí orúkọ rẹ̀ n jẹ́ Donald.Dydy kú ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n, oṣù Kọkànlá ọdún 1939, èyí tí ó jáde láyé látàrí ààrùn jẹjẹrẹ (Cancer).Àwọn àmì ẹ̀yẹfún Ìkópa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Mrs..
wikipedia
yo
Molly O' LEary tí ó jẹ́ ẹ̀yà Catherine O' Leary ní ọdún 1937 ní Chicago, ó gba àmì ẹ̀yẹ Adèmí fún Best Supporting Actress..
wikipedia
yo
Wọ́n yàn láti gba àmì ẹ̀yẹ yìí ná ní ọdún kan fún ìkópa rẹ̀ nínu eré míràn tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "My Man Godfrey..
wikipedia
yo
Awon itan ti a gbo je ki o ye wa pe ni apejọ Valtation funami eye ADemi, okunrin kan ti o wa si gbàgede lati ba Brady gba ami eye Oscar fun Best Supporting Actress ni odun 1943 nitori pe Brady o si nibe lati gba ami eye naa, gba ami naa o si salọ, eyi ti won ko ri, won ko si ri ami eye naa gba lowo re..
wikipedia
yo
Sugbon AkaDemi wa òmíràn lati fi di eyi ti won ko mo fun Brady .Amo gege bi Obasadi ti awon nìí iroyin se, eni ti o dari ere ti o fi gba ami eye naa, Henry King ni o pada ba gba ami naa ni ojo naa, ti awon ore brady pada ba gba lati gbe losi ile ni alẹ ojo naa..
wikipedia
yo
àwọn tí wọ́n já ewé olúborí gba àmì ẹ̀yẹ ṣùgbọ́n lẹ́yìn tí wọ́n gbé délé, wọ́n sì lo dápadà sí Adèmí láti lè jẹ́ kí wọ́n kórùkù sórí àmì ẹ̀yẹ náà..
wikipedia
yo
Eastman House)Miss Petlóriats (1916 World) (Extant; Geo..
wikipedia
yo
Eastman House)The Gilded Catge (1916 World) (Extanttant; Library of Congress, Geo..
wikipedia
yo
Eastman, BFI, London) bought and paid for (1916 World) Losta Woman Alone (1917) Losta Hungry heart (1917) lost the dancer's lọ́dọ̀ (1917) (Extant; DVD grapeVine Video, Geo..
wikipedia
yo
Eastman, Cineca del Friuli)darkest Russia (1917) (inComplete; Library of Congress) Maternity (1917) lost divorce Game (1917) Lostasta self-made Widow (1917) lost Ross (1917) (N extant; Online, grape DVD) a maid of Belgium (1917) Silent Sadu (1917 (1917) (Extant; Library of Congress)Woman and Wife (1918)The knife (1918)The S/ Of Sybil (1918)The trap (1918 World) The Mercy of Men (1918 select)The Ordeal of Rosetta (1918 select) the Whirlpool (1918 select)The Death Dance (1918 select)The better half (1918 (1918)her Great Chance (1918 select)In the hollow of her hand (1918 select) the indestructible wife (1919 select)The End of the Road (1919 Public Health Films)The World to live in (1919 select) Ltd..
wikipedia
yo
(1919 select) Redhead (1919 select)his Bridàljẹ̀ night (1919 select)The fear market (1920 Realart)sinners (1920 Realart)a Dark Lantern (1920 Realart)The New York idea (1920 Realart) (Extanttant; George Eastman House)out of the Chos (1921 Revrt)The Land of Hope (1921 Revrt) lost Italy (1921 Rediert) lost of the East (1921 paraMount Para-Ala lost) lost Money (1921 paraMountth) Lo trip to paraMountown (1922) (E-short) millions (1922 Paramount) Lousna ascends (1922 Paramount) (6 Al Min..
wikipedia
yo
Fragment)The Anaceàwòkẹ́kọ̀ọ́ (1923 Paramount) lost Snow citation (1923 Paramount Paradu) lost Ladies Meet (1933 níbẹ̀m) Beauty N 2016 ( níbẹ̀m) Stage Mother (1933 níbẹ̀m) Broad to Hollywood (1933 níbẹ̀m)The Gay Ficée (1934 Rel)Miss fane's Baby So [ Para ParaMount Diibùsùn of 1935 (1935 Warner Brothers :Let Have It It (1935 United Artists) Smart Girls (1936 Universal) West West, Young Man (1936 Paramount) Man God (1936 Universal)The Har (1936 (1936 Pictures) It a Day Day Warner Brothers Brothers)One hundred men and A Girl (1937 of Old Chicago (1937 20th Century-Fox)
wikipedia
yo
Dodd Takes the Air (1937 Warner Brothers)Goodbye Broadway (1938 Universal)kéde (1939 United Artists)Young Mr..
wikipedia
yo
Lincoln (1939 20th century-Fox)fún kíka Itẹ̀síwájú List of Actors with Academy Award Nominationṣitọ́kasí Shade Literature on Alice Brady Alice Brady Portrait 1910s Alice Brady at the NY Public Library Billy Rose CollectionÀwọn Ọjọ́ìbí ní 1892 Ojolobi ní 1939American Film Actressemerican Silent Film Actresce Stage Act Actbest Supporting Actress Academy Award Winnerss from cancer in New York (State) century Act Souter from New York citYar Containing Video Clíps Theatre Theatre People ẹlẹ́bùn Aodua Obìnrin Òṣèré didara 2
wikipedia
yo
jẹ́ òṣèré tó gba ẹ̀bùn Adèmí bi obinrin òṣèré keji dídárajùlọ.Ìgbésí ayé Arábìnrin Coconnelly ni a Bísí Cairo, New York ni catskill Mountains..
wikipedia
yo
Oṣere lobinrin naa jẹ ọmọ obinrin ilene (dealer ti antique) ati Gérard Karl Connelly (Olùṣẹ̀dá Aṣọ)..
wikipedia
yo
Baba Jennifer jẹ́ ọmọ ìjọ Catholic tó sì wá láti ìran Irish ṣùgbọ́n ìyá òṣèré lobìnrin náà wá láti ìran jẹ́w..
wikipedia
yo
Jennifer dàgbà sí Brooklyn Heights tí ó jìnà sí Brooklyn Bridge.Jennifer fẹ́ bily Campbell tí wọ́n sì pínyà ní ọdún 1996 lẹ́yìn tí wọ́n wà papọ̀ fún ọdún máà.connelly bẹ̀rẹ̀ ìbápọ̀ pẹ̀lú ayaworan David Dugan tó sí ọmọ okùnrin fún ní ọdún 1997.Ní ọdún 2003, Oṣù January ní Jennifer fẹ́ òṣèré lọ́kùnrin Paul Betany ní ìdákẹ́ jẹ́jẹ́ tí wọ́n sì bí ọmọ okùnrin ní ọdún 2003 àti ọmọ obìnrin ní ọdún 2011.ẹ̀kọ́ losi Saint Ann tó jẹ́ ilé ìwé Alaga lóri ìmọ̀ Arts.Lẹ́yìn náà ní òṣèré lóbìnrin náà keko ní ilé ìwé gíga Yale lóri Literature èdè Gẹ̀ẹ́sì ní ọdún 1988..
wikipedia
yo
Leyin odun meji, Jennifer losi ile iwe giga Stanford lórí Drama.Ami eye ati 1979laitọ́kasí awon ẹlẹ́bùn Adèmí obinrin osere didarajùlọ 2k..
wikipedia
yo
jẹ́ òṣèré lóbìnrin ilé Spanish tí a Bìní ọjọ́ 28 oṣù April ní ọdún 1974..
wikipedia
yo
Oṣere lobinrin naa gba ẹbun Adèmí bi obinrin oṣere keji didarajulọ.igbesi aye arabinrin naaCruz ni a bi si Spibendas, Spain fun Encarna SaChez (ẹni tin se irun) ati Eduardo Cruz (olùtajà ati mechanic)..
wikipedia
yo
Cruz gba jumọ ijo, o si ko ballet fun odun mẹsan ni National Conservatory ti Spain.oṣere lobinrin naa keko nipa Ballet ile Spain fun ọdun mẹta ati Theatre ni ile iwe Cristina rọ́ta fun odun mẹrin.lati kekere, Cruz feran Acting nigba ti o ri ere agbelewo "tie me up! tìẹ Me Down! Ni ọdun 1990..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2015, bàbá Cruz kú ní ilé rẹ̀ ní Spain ní ọmọ ọdún meji Leelagọ́tà lórí àìsàn ọkàn.Ní oṣù July, ọdún 2010, Cruz fẹ́ òṣèré lọkunrin ilé Spanish Javier Bardem tí wọ́n sí ọmọ Ọkunrin Leo Fieinas Cruz ní ọdún 2011 si Los Angeles àti ọmọ obìnrin luna welcomedinas Cruz ní ọdún 2013 sí Madrid.Àmì ẹ̀yẹ àti ìdánipelope jẹ́ òṣèré lobinrin ilé Spanish kan ṣoṣo tó ma kọ́kọ́ gba àmì ẹ̀yẹ ADemi.akaṣe ti motion Picture Arts àti Sciences fún Cruz ní àmì ẹ̀yẹ ADemi.Bunepé gba àmì ẹ̀yẹ ADemi Nomination méjì ti British lórí eré àgbéléwò,àmì ẹ̀yẹ Nomination ti Golden Globe, Ami Ẹyẹ Nomination ti Emmy Prime, Ami Ẹyẹ ẹ̀yẹ of oṣere péré Guild ati àmì ẹ̀yẹ The Teve ti àkọsílẹ̀.Ní ọdún 2006, Cruz gba àmì ẹ̀yẹ Òṣèré lobìnrin tó dára jùlọ ní Festival ní Festival lórí eré àgbéléwò
wikipedia
yo
Oṣere lobinrin naa gba ami eye BAFTA gẹgẹbi oṣere lobinrin to dara julọ lori ipa rẹ ninu iranlọwọ.itọkasiàwọn ẹlẹ́bùn Akadèmí obinrin oṣere didarajulọ 2k..
wikipedia
yo
Jane Darwell (tí orúkọ àbísọ rẹ̀ jẹ́ Patti Gd_; tí wọ́n bí ní Oṣù Kẹwàá ọjọ́ karùn-ún , ọdún 1879 tí ó sì kú ní Oṣù Kẹjọ Ọjọ́ Kẹtàlá , Ọdún 1967) jẹ́ òṣèré Amẹ́ríkà lórí orí-ìtàgé, fíìmù, àti tẹ́lẹ̀fison..
wikipedia
yo
O ṣe afihan ni fiimu bi ogorun-un ni fun asiko Ajetúrì die..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ òṣèré tó gba ẹ̀bùn Adèmí bí obìnrin òṣèré kejì tó dára jù lọ.Àwọn Ìtọ́kasíàwọn ẹlẹ́bùn Adèmí obìnrin òṣèré dídára 2K..
wikipedia
yo
jẹ oṣere lobinrin to gba ẹbun Adèmí bi obinrin oṣere keji didarajulọ.igbesi aye arabinrin naaDavis ni a bini ọjọ kejielogun, oṣu January ni ọdun 1956 si Ilu Wahúnham, Massachusetts.Ìyá òṣèré lobìnrin náà Lucille jẹ ẹni to ran olukọ lọwọ ti baba rẹ William f..
wikipedia
yo
Davis jẹ́ Civil Engineer àti DeAcon tí ilé ìjọsìn ti Chris.Nana feran orin lati kékeré tí ó sì kọ́ bí a ṣe lo èrò Piano ato fere ní ilé ìjọsìn ti ChRitaini ní ìlú wareham.Davis fẹ́ Richard EmMolo ní Oṣù March ní ọdún 1981 tí wọ́n sì pínyà ní Oṣù June ní ọdún 1984..
wikipedia
yo
Ní 1985, òṣèré lobìnrin náa fẹ́ òṣèré lọ́kùnrin Jeff Goldblum ní Oṣù November ní ọdún 1987 tí wọ́n sì pínyà ní Oṣù October ní ọdún 1990.Ní ọdún 1993, Ngee fẹ́ Gavin De Becker tí wọ́n sì pínta ní ọdún 1998.Ní ọdún 2001, Davis fẹ́ Reza Jarated tí wọ́n sí ọmọ mẹ́ta; ọmọ obìnrin obìnrin kan Alid (tí a Bìní Oṣù April ní ọdún 2002), olùbejì Kai àti Kian (an A bini Oṣù May ní ọdún 2004–
wikipedia
yo
Awon toko taya naa pinpin ni osu May, odun 2018 da ojogbonna Davis Institute sile ni odun 2007.Ekoesena losi ile eko Wareham to si gba ibe losi Svikenken ni ilu Sweden nibi to ti mo ede Sweden so dara dara..
wikipedia
yo
Oṣere lobinrin tun keko ni College ti New England sugbon ko le pari degree re lori ere Oritage ni ile iwe giga ti Boston ni odun 1979.Ami eye ati 1980laitọ́kasíàwọn ẹlẹ́bùn Adèmí obinrin osere didarajulọ 2k..
wikipedia
yo
Jẹ oṣere lobinrin to gba ẹbun Adèmí bi obinrin oṣere keji didarajulọ.Ìgbésí ayé arabinrin náàdench ni a bini Heworth Area ti York ni ọdun 1934 fun eleanora Olive ati Reginald Arthur dench to jẹ Dokita (1897-1964)..
wikipedia
yo
Iya osere lobinrin naa wa lati iran Irish ti a si Bisi Dublin sugbon baba rẹ wa lati iran ede Geesi to dagba si Dublin to si ja ni Western Front ni Ogun Àgbáyé akọkọ.Ni oṣu March ti ọdun 2013, Dench ni a kà gegebi okan lara awon aadota to mo aso wo julọ to si ti ju ọmọ ọdun aadota lọ..
wikipedia
yo
Dench jẹ́ Olubùkún ati olùgbèjà ti Liverpool tí bọ́ọ̀lù afẹsẹgba F.C.dench fẹ́ Michael Williams tó jẹ́ òṣèré lànalò láti Liverpool ní ọdún 1971 tí wọ́n sì bí ọmọ obìnrin Finty Williams (òṣèré lóbìnrin) ní ọdún 1972..
wikipedia
yo
Michael kú lórí àìsàn jẹjẹrẹ ti lung ní ọdún 2001.Lẹ́yìn ọkọ dench ni ó fẹ́ David Mills ní ọdún 2010..
wikipedia
yo
Dench jẹ́ ẹni tó tako ọ̀rọ̀ nípa àwọn òṣèré lobìnrin tó ti dàgbà tí wọ́n sin Ṣiṣẹ́.Èkóch lọ sí ilé ìwé Mount tó jẹ́ ilé ìwé Quaker independent ní York tó sì padà di Quaker..
wikipedia
yo
Oṣere lobinrin naa losi ile iwe Central fun Oro ati Drama nibi to ti gba ebun ere sise merin pelu Gold Medal gegebi Eko to pegede ju.Ami eye ati yínfohunch gba ami eye Adèmí gegebi osere lobinrin to Rani lowo julo lori ipa re gegebi Queen Elizabeth i ninu ere Ife, Ami eye Academy lori ere ti British mefa, Ami eye BAFTA, Ami eye Oscar, Ami Ẹyẹ Akadèmí Television ti British mẹrin, Ami eye osere screen Guild meji, Ami Ẹyẹ Tony ati ami eye Laurence Olivier meje.Dench ni a fi je Officer ti order ti British Empire ni odun 1970 ati Dame commander ti order ti British Empire ni odun 1988.oṣere lobinrin naa ti gba ìdaBasket ti Commonwealth ati degree.Awon ẹlẹ́bùn Akadèmí obinrin osere didara 2k..
wikipedia
yo
Sandra dalẹ̀ Dennis (Oṣù kẹrin ọjọ́ kẹtà-din-lọ́gbọ̀n, ọdún 1937 sí oṣù kẹta ọjọ́ kejì, ọdún 1992) jẹ́ òṣèré obìnrin ti ilẹ̀ Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Ó ṣe àṣeyọrí nínu fíìmù tó gbé e jáde, “Ppledor in the Grass” (ọdún 1961)..
wikipedia
yo
Fíìmù tó farahan gbẹ́yín wà ní dírámà Adágún "The Indian runner" (ọdún 1991).Dennis ni iṣẹ́ àṣeyọrí nínu iṣẹ́ rẹ̀ lórí ìtàgé, ifarahan sise ere itage gangan ti "Come back to the Five and Dime, Jimmy Dean..
wikipedia
yo
Fun iṣe rẹ ninu jara"a thousand clowns, ó gba ẹ̀bùn àmì ẹ̀yẹ Tony fún òṣèré obinrin tó farahàn tó dára jùlọ..
wikipedia
yo
Fun iṣẹ rẹ ninu ere"Any Wednesday", o gba ebun ami eye Tony fun osere obinrin to dara julo ninu ere naaìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ aye rẹwọn bi Dennis ni Hastings, Nebraska, omo Yvonne (née Hudson), to je eyi ti awon oyinbo n pe ni "secretary", pelu Jack Dennis, eyi ti awon oyinbo maa n pe ni "Postal Clerkk"
wikipedia
yo
Dennis dàgbà ní Kenesaw, Nebraska, àti Lincoln Nebraska, tí ó jáde láti ilé-ìwé gíga Lincoln High School ní ọdún 1955; ọ̀kan nínu àwọn ọmọ tí wọ́n jọ wà ní Kíláàsì jẹ́ Akọ̀wé pẹ̀lú apanilẹ́rìn-ín, Dick Cavett..
wikipedia
yo
Ó lọ sí Fásitì Nebraska Wesleyan àti Fásitì ti Nebraska, fífarahàn nínú ẹgbẹ́ ìtàgé Lincoln kí ó tó di pé ó kó lọ New York ní ọjọ́ orí ọ̀kan-dín-lógún..
wikipedia
yo
Ó kó eré ṣíṣe ní HB Studio ní ilẹ̀ New York.Ikú rẹ̀Sandy Dennis kú nípasẹ̀ àìsàn ara kan tí Òyìnbó n pè ní "Ovarian Cancer" ní Oṣù kẹta ọjọ́ kejì, ọdún 1992, ní ilé rẹ̀ ní Westport, Connecticut, ní ọjọ́ orí erin-lé-kú-kú.Àwọn iṣẹ́ rẹ̀fífíàwọn ìtọ́ka sí..
wikipedia
yo
Ni won bi ni ojo kejiilelogun, osu kefa odun 1931 , ti o si dágbére Lo ni ojo Kero, osu karun, odun 2021) je òṣèrébìnrin orílẹ̀ èdè America tó gba ẹ̀bùn ADemi ti obìnrin osere kejì didarajulọ nígbà ayé rẹ̀.Igba Ewe ati bi o ṣe kẹ́kọ̀ọ́won bi Olympia Durative si Lowell, Massachusetts lọ́jọ́ ọjọ́ kejìilelogun, osu kefa ọdún 1931 sínú ìdílé Alexandra Aleation (Nee Christos) àti Constantine Costa S..
wikipedia
yo
Dukis jẹ́ akẹkọjáde ilé ẹ̀kọ́ ti Arlington High School, Arlington, Massachusetts, tí ó si tẹsiwaju lọ sí Yunifásítì Boston.Filàwọn fíìmù tí ó ti kọpaahùnhùnàwọn ìtọ́kasíàwọn ẹlẹ́bùn Adèmí obinrin òṣèré dídárajùlọ 2k..
wikipedia
yo
Anna Marie "Patty" Duke tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìnlá Oṣù kejìlá Ọdún 1946 , tí ó sì dágbére Faye ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n, Oṣù Kẹta, Ọdún 2016 jẹ́ òṣèrébìnrin orílẹ̀ èdè America tó gba ẹ̀bùn Adèmí tí obìnrin òṣèré kejì dídárajùlọ, Golden Globe Awards léméjìi Otọ̣́tọ̀, Primetime Emmy Awards lémẹ́ta nígbà ayé rẹ̀.Ìbẹ̀ṣe ayé rẹ̀ Duke ni wọ́n bí sí ilé-ìwòsàn Belẹ̀sìn ní Manhattan sí Ìdílé Francis Margaret (Nee McMa) 1913-1993) àti John Patrick Duke (1913-1964). Àwọn ẹbun àti àmì ẹ̀yẹ ẹlẹ́bùn Abọ̀wọ̀ obìnrin obìnrin dídùndé 2
wikipedia
yo
Brenda Fricker (tí a bí ní ọjọ́ kẹtà-din-logun ọdún 1945) jẹ́ òṣèré Irish kan, tí iṣẹ́ rẹ̀ ti kọjá ọgbọ̀n ọdún ní orí ìtàgé àti lórí ojú ìtara..
wikipedia
yo
O ti farahan ni fiimu ati awọn ipo ifihan to ju ọgbọ̀n lọ..
wikipedia
yo
Ni ọdun 1990, o di oṣere Irish akọkọ lati gba aami-ẹri ile-ẹkọ giga kan, ti o gba ẹbun naa fun oṣere atilẹyin ti o dara julọ fun "My Left foot” (ni ọdun 1989)..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2020, o wa lori nọmba àpọ́sítélì-din-lọgbọn lori Akojọ orukọ ti Irish Times ti awọn oṣere fiimu nla ti ilẹ̀ Ireland.ibẹrẹ aye rẹa bi Fricker ni Dublin, ilẹ̀ Ireland..
wikipedia
yo
Iya rẹ, "agb" (Nee Murphy), je olukọ ni ile iwe giga lórípà, ati baba rẹ, Desmond Frederick Fricker, sise ni ẹka ogbin bii 'Fred Desmond' Olugbohun-safefe pelu RTÉ ati oniroyin fun The Irish Times.ṣaaju ki o to di oṣere, Fricker jẹ oluranlowo si olootu aworan ti Irish Times, pelu ìrètí a ti di oniroyin..
wikipedia
yo
Ni igba to pe okan-din-logun ni ojo-ori, o di oṣere “nipasẹ aye” Iṣẹ fiimu ẹya rẹ bẹrẹ pẹlu apa kan ti ko ni àpọnlé ninu fiimu 1964 1964 Human Bondage, ti o da lori iwe aramada odun 1915 nipasẹ W..
wikipedia
yo
O tun farahan ni yatoka row, soap opera akoko ti Ireland.Ayé re Fricker lọwọlọwọ ngbe ni Liberties, Dublin..
wikipedia
yo
O sọ pe awọn ifẹ rẹ pẹlu awọn aja ọsin rẹ, mimu Guinness, kika ewi ati ṣiṣa Snooker (o sọ ni igba kan pe o ti gba gbogbo àwọn ara osere ti "My Left foot"
wikipedia
yo
“Mo se adagun-odo si ẹẹ́ta-din-logun ninu wọn, mo si lu gbogbo won," Brenda wi).Awon ere to ti se{| class="wikìtà Sortable " Year! Title! Role Class="unsortable ↑ notes:|-| 1964| of human Bondage UnREDIted| 1969| sinful Davey|| unREDIted: 1975| UPOPOWE, Downton| | UnDIted (Extra) 1977| 1977ọrọ Nation Street | staff nurse málòce| 4 episode Arc| 1978-1979| the 6terland conclusion | Alison Thorpe| Television series: 1979| the music Machine| Mrs..
wikipedia
yo
(tí a bí ní Oct 30, 1986, tí òsì fi ayé sílẹ̀ ní August 28, 1985) jẹ́ òṣèrébìnrin àti olùkọ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà, ó gba ẹ̀bùn Adèmí fún obìnrin òṣèré kejì dídárajulọ...
wikipedia
yo
O tún kọ́ kó ọ̀pọ̀lọpọ̀ èrè àti ìwéàárọ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹa bí Ruth Gordon ní agbègbè 41 Winthrop Avenue ti ìlú Quincy, Massachusetts..
wikipedia
yo
Ó padà gbé ní agbègbè 41 Marion Street (1901-1903) àti 14 Elmwood Avenue (1903–1914) ti ìlú Kanaa..
wikipedia
yo
A bí sínú ìdílé Annie Tapley àti Clinton Jones, òun nìkan ni ìyá àti bàbá rẹ̀ by papọ̀, bó tilẹ̀ jẹ́ wípé bàbá rẹ̀ ti bí ọmọbìnrin kan ní ìgbéyàwó rẹ̀ àkọ́kọ́, ẹni tí orúkọ rẹ̀ njẹ́ Claire.Igba tó kọ́kọ́ di ìlú mọ́ mi ní ìgbà tí wọ́n lo àwòrán rẹ̀ ní ìpolówó kan tí ọ̀gá bàbá rẹ̀ ṣe fún ilé-iṣẹ́ Mellin's Food for Innaà and Alialids.Nígbà tí ó wà ní ilé-ìwé Quincy High School, ó kọ lẹ́tà sí ọ̀pọ̀lọpọ̀ òṣèrébìnrin fún àwòrán wọn tí wọ́n jàn ní òunte, ìhùn tí òṣèrébìnrin Hazel Dawn fún Lẹ́tà rẹ̀ ru lọ́kàn sókè láti di òṣèrébìnrin..
wikipedia
yo
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé bàbá rẹ̀ ń ṣe iyè méjì nígbà ṣíṣe rere rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣèré, ó fi ìgbàgbọ́ mú Ruth lọ sí ilé-ìwé American ACedemy of Dramatic art tí ó wà ní New York ní ọdún 1914.Iṣẹ́ Rúnjẹ ọdún 1915, Gordon farahàn ní eré kan tí wọ́n ṣe nípa Vernon and Irene Castle..
wikipedia
yo
Ní ọdún kanàá, ó ṣe eré nínú fíú Peter P.Ní ọdún 1918, Gordon àti Gregory Kelly ṣeré nínú fíú tí àpèlé rẹ̀ jẹ́ Seventeen ní ọdún 1920, Gordon lọ sí ilé ìwòsàn kan ní ìlú Chicago níbi tí wọ́n ti kan egungun ẹsẹ̀ rẹ̀ tí wọ́n sì ti tó padà, wọ́n ṣe yí láti mú kí ẹsẹ̀ rẹ̀ tó wọ̀ tẹ́lẹ̀ dúró.Àwọn ìtọ́kasíàwọn ẹlẹ́bùn Adèmí obìnrin òṣèré dídárajùlọ 2k..
wikipedia
yo
jẹ oṣere lobinrin ati akọrin ilẹ̀ America to gba ẹbun Adèmí bi obinrin oṣere keji didarajulọ.igbesi aye arabinrin GGhámì ni a Bisi Los Angeles..
wikipedia
yo
Baba Gloria Reginald Michael Bloexam jẹ́ fẹjútect ti ilẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì àti Olùkọ̀wé ṣùgbọ́n ìyá rẹ̀ Jean McDoudou jẹ́ òṣèré lobinrin ilé British.Ghámì jẹ́ Democrat tó ti Adlai Stevenson lẹ́yìn lori Campaign rẹ̀ lori idibo are ni ọdun 1952.Ghámì fẹ́ ọkọ lẹ́ẹ̀mẹ́rin to si bi ọmọ Merim..
wikipedia
yo
Oṣere lobinrin naa se igbeyawo akọkọ pẹlu oṣere lọkunrin Stanley Clements ni Oṣu August, ọdun 1945..
wikipedia
yo
To taya pínyà ní ọdún 1948.Láìsí fẹ́ director Nicholas Ray tí wọ́n sì bí ọmọ ọkùnrin Timothy ní oṣù November, ọdún 1948..
wikipedia
yo
To taya Pínyà ní ọdún 1952.Òdodo ṣe ìgbéyàwó kẹta pẹ̀lú Olùkọ̀wé àti Olùdarí Television Cy Howard ní oṣù August, ọdún 1954 tí wọ́n sì bí ọmọ obìnrin Marianna Paulette ní ọdún 1956..
wikipedia
yo
Tọ́kọ taya Pínyà ní Oṣù November, Ọdún 1957.Gloria ṣe ìgbéyàwó kẹrin pẹ̀lú òṣèré lọkùnrin Anthony Ray (ọmọ ọkọ rẹ̀ ẹlẹ́kejì) ní oṣù May, ọdún 1960 tí wọ́n sì bí ọmọ ọkùnrin méjì; Anthony ní ọdún 1963 àti James ní ọdún 1965.Ní oṣù March, ọdún 1974 Gloria ni àrùn jẹjẹrẹ ti ọmú..
wikipedia
yo