raw_text
stringlengths 2
128k
|
---|
onueke onueke je ìlú ní nàìjíríà |
òpobò opobo je ìlú ní nàìjíríà |
orerokpe orerokpe je ìlú ní nàìjíríà |
orhuwhorun orhuwhorun je ìlú ní nàìjíríà |
oron nàìjíríà oron nàìjíríà je ìlú ní nàìjíríà |
orlu orlu je ìlú ní nàìjíríà |
osubi osubi je ìlú ní nàìjíríà |
otu jeremi otu jeremi je ìlú ní nàìjíríà |
ovwian ovwian je ìlú ní nàìjíríà |
ozoro ozoro je ìlú ní nàìjíríà |
potiskum potiskum je ìlú ní nàìjíríà |
sango otta sango otta jé ìlú olórúkọ ní ìpinlẹ̀ ògùn nàìjíríà |
ṣẹ̀pẹ̀tẹ̀rí nàìjíríà ṣẹ̀pẹ̀tẹ̀rí nàìjíríà jẹ ìlú to tobi jù ni ìjọba ìbílẹ̀ gúsù ṣakí ti oke-ogun ìpínlè ọ̀yọ́ nàìjíríà àwọn ọmọ yorùbá ti ṣẹ̀pẹ̀tẹ̀rí tan mọ àwọn ifọn ti dahomey ati àwọn ifọn ni ìpínlẹ̀ ọ̀ṣun olóyè wọn ọba ìlú náà wá lati ìdílé obàtálá ọbàlùfọ̀n ti ọ̀yọ́ ile ṣẹ̀pẹ̀tẹ̀rí duro láàrin igboho ago-amodu ati oje owode ti won pe ni aha tele saki ago-are ati iseyin apejuwe orúkọ ti ọba ṣẹ̀pẹ̀tẹ̀rí njẹ ni ọbalùfọ̀n ti ṣẹ̀pẹ̀tẹ̀rí awọn ìdílé to nṣe jọba ni daodus baloguns ati ogboros o wà ni àárin ṣakí ati ìgbòho ni agbègbè oke-ogun òyó arewa senatorial district ti ilu oyo ni yorùbá oke-ogun ni ìjọba kẹkẹ mewa àyàfi ògbómọ̀ṣọ́ oke-ogun bẹẹ láàrin òyó ati ìpínlè kwara lọwọlọwọ agbègbè ṣẹ̀pẹ̀tẹ̀rí bèèrè lati ìséyìn osi lópin ni bakase ilu kékeré kan pelu ààlà ti ìpínlè òyó ati ìpínlè kwara awon ara ilu ilu jẹ ibarapọpọ ti o ni akọkọ awọn eniyan ti o jẹ ti ẹya yoruba ti wọn sọ ede yoruba botilẹjẹpe awọn ẹgbẹ to kere lati ibomiiran ni nigeria ati afirika ni aṣoju bii gbogbo awọn ọmọ yoruba miiran wọn jẹ ọmọ lati oduduwa eto idile ti o gbooro se pataki si asa ati igbagbo ile yoruba iṣowoedit source wiwa ti nkan àlùmọnì wà ni agbègbè bíi tantalite columbite cassiterite kaolin ati granite ìjọba ìpínlè òyó ti n ṣètò lapidary kan lati toju awon nnkan àlùmọnì ati ọjà òkúta iyebiye ni káríayé ni ìlú ìbàdàn níbití àwọn iwakusa le ṣe ta ọja wọn iṣẹ àgbẹ̀ ni iṣẹ àwọn ọmọ ìlú ṣẹ̀pẹ̀tẹ̀rí yàtò si àwọn ipa àkọkọ́ ti pipesè oúnjẹ ati ibi ààbò oojọ awọn ohun èlò aiṣe ile-iṣẹ o tun jẹ orísun pàtàkì ti owo-wiwọle ni ìjọba agbègbè |
sepeterinigeria |
suleja suleja je ìlú ní ipinle niger nàìjíríà |
surulere lagos state surulere lagos state je ìlú ní nàìjíríà |
udu nàìjíríà udu nàìjíríà je ìlú ní nàìjíríà |
ughelli ughelli je ìlú ní nàìjíríà |
ukat aran ukat aran je ìlú ní nàìjíríà |
wukari wukari je ìlú ní nàìjíríà |
yaba yaba je ìlú ní nàìjíríà |
frederick lugard british colonial administrator 18581945 frederick john dealtry lugard 1st baron lugard 22 january 1858 11 april 1945 tí wọ́n mọ̀ sí sir frederick lugard láàárín 1901 àti 1928 jẹ́ jagunjagun british alágbàṣe olùwákiri áfíríkà àti alámòójútó ìjọba amúnisìn ó jẹ́ gómìnà hong kong tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀ rí 19071912 gómìnà ìkẹyìn southern nigeria protectorate 19121914 kọmíṣọ́nà gíga àkọ́kọ́ 19001906 àti gómìnà ìkẹyìn 19121914 northern nigeria protectorate àti adarí gómìnà nàìjíríà 19141919 àkọ́kọ́ ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ wọ́n bí lugard ní madras chennai nísìnyí ní india ṣùgbọ́n wọ́n tọ́ ọ ní worcester england ó jẹ́ ọmọkùnrin reverend frederick grueber lugard àlùfáà àwọn ológun bírítéènì ní madras àti ìyàwó rẹ̀ kẹtà mary howard 18191865 ọmọbìnrin reverend john garton howard tí ó kéré jùlọ 17861862 ọmọkùnrin kékeré ọmọọnílẹ̀ láti thorne àti melbourne nítòsí york arákùnrin bàbá rẹ̀ ni sir edward lugard adjutant-general in india láti 1857 sí 1858 àti permanent under-secretary of state for war ní ilé-iṣẹ́ ogun láti 1861 di 1871 lugard kẹ́kọ̀ọ́ ní rossall school àti royal military college sandhurst orúkọ 'dealtry' jẹ́ ìmọrírì thomas dealtry ọ̀rẹ́ bàbá rẹ̀ |
gombe state |
ipinle gombe |
joseph orji joseph orji je gomina ipinle gombe lati october 7 1996 titi de august 1998 |
mohammed bawa mohammed bawa 6 april 1954 26 may 2017 je gomina ipinle gombe lati august 1998 titi de may 1999 |
abubakar habu hashidu abubakar habu hashidu je gomina ipinle gombe lati may 29 1999 titi de may 29 2003 |
jobele jobele je ilu kekere ni ipinle oyo ni naijiria ilu yi ni ibujoke agbegbe ijoba ibile afijio |
àwọn ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin látin ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ the nigerian national assembly delegation from oyo comprises three senators representing oyo south oyo central oyo north and fourteen representatives representing the following federal constituencies ona-ara/egbeda iseyin/kajola/iwujola/itesiwaju ibadan north- east/south- east lagelu/akinyele ibarapa east/ido ibadan north oluyole atigbo/saki east/saki west ibadan north west/south west ibarapa central/ibarapa north afijio/atiba/oyo east/oyo west ogo-oluwa/surulere oluyole ogbomosho-north/south/orire and olurunssogo/orelope/irepo |
ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ile-igbimo asofin ipinle oyo ni apa ijoba ipinle oyo to n se ofin ni ipinle na gege bi ilana-igbagbepo naijiria 1999 se so |
oyo state house of assembly |
taofeek oladejo arapaja taofeek oladejo arapaja je oloselu omo ile naijiria ati igbakeji si gomina ipinle oyo adebayo alao-akala lati 2007 teletele o je asoju ni ile-igbimo asofin naijiria fun ibadan south-west/ibadan north-west constituency lati 2003 de 2007 ati alaga agbegbe ijoba ibile guusu-iwoorun ibadan ni 1999 de 2003 |
ìwé ìkọjá nàìjíríà |
plateau state |
sokoto state <ns>0</ns> <revision> <parentid>69258</parentid> <timestamp>2024-02-01t010429z</timestamp> <contributor> <username>emausbot</username> </contributor> <minor /> <comment>fixing double redirect to ìpínlẹ̀ sokoto</comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> |
jty aguyi-ironsi |
agbegbe apaariwa naijiria |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ gúúsù idemili agbegbe ijoba ibile guusu idemili je ijoba ibile ni ipinle anambra ni naijiria ibujoko re wa ni ojoto |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ido-osi agbègbè ìjoba ìbílè ìdó-òsi jé ìjoba ìbílè ní ìpínlè èkìtì tó wà ní nàìjíríà ibùjókò ó rè wà ní ìlú u ìdó-òsi ìtókasí ìdó-òsi wà ní ìpínlè èkìtì l'órílè èdè nàìjíríà ìjoba ìbílè ná à kún fún àwon ìlú àti ìletò àtètèdáyé tí ó kúndùn-un èkó kíkó tí wón sì ní ìdáméwà á àkójopò o àwon òmòwé gíga yíká órílè èdè ná à tó sì tún jé òkan nínú u agbègbè ìjoba ìpínlè èkìtì ó sún mó àwon agbègbè ìjoba mìíràn bí i mòbà ìjerò ìlejeméje àti adó ìjoba ìbílè yì í ní àwon ìlú wònyì í l'ábé e rè àayè ìdó ùsì ayétòrò ìlógbò òsi ìfàkì òrìn odò-orà òkè-orà ìlógbò igbólé àti àwon ìletò kéréje-kéréje bí i ìpólé òbajì odò obà-aládélúsì òkálàwá òkè esè tèmigbolá òrìn àayè ìfisìn òrà olú ilé işé ìjoba ìbílè yì í ni wón fi s'odo si ìdó èkìtì tí ilé ìşàkóso sì wà ní àárín-in ìlú ìdó àti ùsì láàrín-in àwon akegbé e rè ní ìpínlè èkìtì ìdó-òsi ní awon onímò ìwe dunjú l'átàrí i àtètèdá a ìlé ìjosìn àti ilé èkó alákòóbèrè s'ílù ú ùsì èkìtì ní kété tí ilé èkó o ti adó èkìtì tí ń şe olú-ìlù ìpínlè ná à gbin'lè lára àwon ènìyàn pàtàkì àti òtòkùnlú ìlú láti ìjoba ìbílè ná à lati rí gómìnà ìpínlè ná à télè rí olúşégun òní enití ó wá láti ìlú ìfàkì |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ifako/ijaye agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ifako/ijaye wa ni naijiria |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ifedayo agbegbe ijoba ibile ifedayo je ijoba ibile ni ipinle osun ni naijiria ibujoko re wa ni oke-ila |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ifedore agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ifedore wa ni naijiria |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ifelodun ìpínlẹ̀ kwárà agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ifelodun ìpínlẹ̀ kwárà wa ni naijiria |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ifelodun ìpínlẹ̀ ọ̀ṣun agbegbe ijoba ibile ifelodun je ijoba ibile ni ipinle osun ni naijiria ibujoko re wa ni ìkìrun |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ifo agbegbe ijoba ibile ifo je ijoba ibile ni ipinle ogun to wa ni naijiria |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ igabi agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ igabi wa ni naijiria |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ igalamela-odolu agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ igalamela-odolu wa ni naijiria |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ igbo-etiti agbegbe ijoba ibile igbo-etiti je ijoba ibile ni ipinle enugu towa ni nigeria ibujoko re wa ni ilu ogbede |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ àríwá igbo-eze agbegbe ijoba ibile ariwa igbo-eze je ijoba ibile ni ipinle enugu towa ni nigeria ibujoko re wa ni ilu enugu-ezike |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ gúúsù igbo-eze agbegbe ijoba ibile guusu igbo-eze je ijoba ibile ni ipinle enugu towa ni nigeria ibujoko re wa ni ilu ibagwa-aka |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ iguegben agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ iguegben wa ni naijiria |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ihiala agbegbe ijoba ibile ihiala je ijoba ibile ni ipinle anambra ni naijiria ibujoko re wa ni ihiala awon ilu miran ni agbegbe ijoba ibile yi ni okija ati uli |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ihitte uboma agbegbe ijoba ibile ihitte/uboma je ijoba ibile ni ipinle imo ni naijiria ibujoko re wa ni isi nweke |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ilaje agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ìlàjẹ jẹ́ ìjọba-ìbílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ òǹdó tó wà ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà olú-ìlú rẹ̀ gúnwà sí ìlú igbokoda àwọn ìlájẹ jẹ́ ẹ̀yà tí ó dá yàtọ̀ tí wọ́n ṣẹ̀ sí etídò àwọn ẹ̀yà elédè yorùbá tí wọ́n tàn yíká etí odò ìpínlẹ̀ òndó ògún èkó àti delta |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ìlàòrùn ijebu agbegbe ijoba ibile ilaorun ijebu je ijoba ibile ni ipinle ogun to wa ni naijiria |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ àríwá ijebu agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ àríwá ijebu wa ni naijiria |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ àríwá-ìlàòrùn ijebu agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ àríwá-ìlàòrùn ijebu wa ni naijiria |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ijebu-ode agbegbe ijoba ibile ijebu-ode je ijoba ibile ni ipinle ogun to wa ni naijiria |
agbegbe ijoba ibile ijebu-ode |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ijero agbegbe ijoba ibile ijero je ijoba ibile ni ipinle ekiti towa ni nigeria ibujoko re wa ni ilu ijero-ekiti |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ijumu agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ijumu wa ni naijiria |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ika-annang agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ika-annang wa ni naijiria |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ àríwá-ìlàòrùn ika agbegbe ijoba ibile ariwa-ilaorun ika je ijoba ibile ni ipinle delta ni naijiria |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ikara agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ikara wa ni naijiria |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ gúúsù ika agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ gúúsù ika wa ni naijiria |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ikeduru agbegbe ijoba ibile ikeduru je ijoba ibile ni ipinle imo ni naijiria ibujoko re wa ni iho |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ikeja agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ikeja wa ni naijiria |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ìkẹ́nnẹ́ agbegbe ijoba ibile ikenne je ijoba ibile ni ipinle ogun to wa ni naijiria |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ikere agbegbe ijoba ibile ikere je ijoba ibile ni ipinle ekiti towa ni nigeria ibujoko re wa ni ilu ikere-ekiti |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ikole agbegbe ijoba ibile ikole je ijoba ibile ni ipinle ekiti towa ni nigeria ibujoko re wa ni ilu ikole-ekiti |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ikom agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ikom wa ni naijiria |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ikono agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ikono wa ni naijiria |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ìkòròdú agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ìkòròdú wa ni naijiria |
umaru farouk abdul mutallab umaru farouk abdul mutallab je omo orile-ede naijiria to je fifesunkan pe o tiraka lati yin bombu abefanka ninu ifoloke 253 baalu ti northwest airlines ni ojo keresimesi december 25 2009 |
abdulfarouk umar muttalab |
umar farouk abdul mutallab |
saint petersburg |
bozhe tsarya khrani |
petrograd |
èdè fínlándì finnish or suomen kieli |
pétérù 1k ilẹ̀ rọ́síà peter i the great or pyotr alexeyevich romanov rọ́síà |
finnish language |
rómù olómìnira orílẹ̀-èdè olómìnira àwọn ará rómù latini res publica romanorum ni a n pe igba itan romu ti awon ara romu le oba ikeyin won kuro lori ite lati sepilese oselu igba oselu tabi igba olominira bere pelu iwolulo oba tokeyin ara etruski eyun tarkuinu onigberaga tarquinius superbus ni 509 kj o si dopin pelu ibori oktabiani lori marku antoni ni ija aktiomu ni 31 kj |
roman republic |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ikot-abasi agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ikot-abasi wa ni naijiria |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ikot ekpene agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ikot ekpene wa ni naijiria |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ikpoba-okha agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ikpoba-okha wa ni naijiria |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ikwerre agbegbe ijoba ibile ikwerre je ijoba ibile ni ipinle rivers ni naijiria ibujoko re wa ni isiokpo |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ikwo agbegbe ijoba ibile ikwo je ijoba ibile ni ipinle ebonyi ni nigeria |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ikwuano agbegbe ijoba ibile ikwuano wa ni naijiria |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ila agbegbe ijoba ibile ila je ijoba ibile ni ipinle osun ni naijiria ibujoko re wa ni ila orangun |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ilejemeje agbegbe ijoba ibile ilejemeje je ijoba ibile ni ipinle ekiti towa ni nigeria ibujoko re wa ni ilu iye-ekiti |
ile oluji ile oluji wà ní nàìjíríà ìpínlẹ̀ ilẹ̀ olúji jẹ́ ìlú kan ní ìpínlẹ̀ ondo orílẹ̀-èdè nigeria ìlú yìí jẹ́ olú- ìlú fún ìpínlẹ̀ ile-oluji/okeigbo àwọn ìlú náà jẹ́ ọmọ yorùbá tí babańlá wọ́n jẹ́ oduduwa jegun of ile-oluji orúkọ ọba wọn hrm oba dr oluwole olufaderin adetimehin fiin fcib jimoko ii tí ó jẹ́ olórí ilé-ìfowópamọ́ chartered insurance institute of nigeria tẹ́lẹ̀ rí ni ọba wọn tuntun tí wọ́n dé ládé ní ọjọ́ kẹwàá oṣù kẹfà ọdún 2016 ètò -ọrọ̀-ajé ile-oluji jẹ́ ìlú tí ó fàyè gba ètò- ọ̀gbìn ó jẹ́ ọkàn lára ìlú tí ó ń ṣe kòkó jù lọ ní orílè-èdè nàìjíríà tí ó sì ń gbé e lọ sí àwọn orílè-èdè mìíràn ẹ̀gẹ́ iṣu àgbàdo àti epo pupa jẹ àwọn ohun ọgbìn tí àwọn àgbè ìlú yìí tún máa ń tẹpele mọ́ ilé-iṣẹ́ tó ṣe pàtàkì jù ní ìlú yìí ni cocoa products ile-oluji limited ó ní ọkàn nínú àwọn ilé-iṣẹ́ tó máa ń ṣe kòkó jù lọ ní ìwọ̀-oòrun áfíríkà àwọn òhun tí ilé iṣẹ́ yìí ń ṣe ni cocoa powder cocoa cake cocoa butter àti cocoa liquor èyí tí wọ́n tà fún àwọn oníbàárà wọn lára àwọn oníbàárà wọ́n ni promasidor nigeria nestle fan milk indcresa productos del cacao ní spain àti theobroma bv ní netherlands oluji pure cocoa powder jẹ́ ọ̀kan lára ohun tí ilé-iṣẹ́ yìí ṣe ètò-ẹ̀kọ́ ilé-ìwé gíga ìjọba àpapọ̀ pólì federal polytechnic ile-oluji ni ilé-ìwé gíjà tó jẹ́ gbòógì ní ìlú yìí ilé-ìwé ìkọ́ṣẹ́ asiwaju bola tinubu skills acquisition centre tí ìjọba àpapọ̀ nàìjíríà kọ́ wà ní 'ilẹ̀-olúji gboluji grammar school ile-oluji jẹ́ ọkàn lára ọgọ́rùn-ún ilé-ìwé girama tó ti pẹ́ ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà àwọn ilé-ìwé girama mìíràn ní ìlú yìí ni holy saviour's high school orere grammar school baptist high school cac grammar school st francis college gloryfield international college new era high school àti akinyosoye model college àwọn ènìyàn tó lààmìlaaka ní ile oluji àwọn ènìyàn wọ̀nyí jẹ́ àwọn ènìyàn tó lààmìlaaka tí wọ́n bi tí ó gbé tí ó sì ń gbé ní ile-oluji lọ́wọ́lọ́wọ́ |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ìlàòrùn ilesa ìlà oòrùn iléṣà jẹ́ agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ ọ̀ṣun ní naijiria olú ilé ìjọba ìbílẹ̀ náà wà ní iyemogun ni ìlú ilésà agbègbè náà tóbi tó 71 km² tí àwọn ènìyàn inú rẹ̀ sí jẹ́ 106586 nígbà ìkànìyàn ọdún 2006 kóòdù ìfìwéránṣé agbègbè yí sì jẹ́ 233 |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ìwọòrùn ilesa agbegbe ijoba ibile iwoorun ilesa je ijoba ibile ni ipinle osun ni naijiria ibujoko re wa ni ereja |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ illela agbegbe ijoba ibile ariwa illela je ijoba ibile ni ipinle sokoto ni naijiria ibujoko re wa ni illela |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ìlàòrùn ilorin agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ìlàòrùn ilorin wa ni naijiria |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ gúúsù ilorin agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ gúúsù ilorin wa ni naijiria |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ìwọòrùn ilorin agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ìwọòrùn ilorin wa ni naijiria |
agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ imeko-afon ìjọba ìbílẹ̀ ìmẹ̀kọ-àfọ̀n jẹ́ ìjọba-ìbílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ ògùn lórílẹ̀ èdè nàìjíríà |