cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ètò ìbílẹ̀ lábẹ́ àṣẹ ògbóni àti Parakoyi 1830–1865Ẹ̀gbá United Board of Management 1865-1898 United Government (Ìjọba Ẹ̀gbá) 1898 – 1914Ẹ̀gbá Native Administration (Ìjọba ìbílẹ̀) 1914 – 1960 Àwọn Ẹ̀gbá Iṣẹ́ Iṣẹ́ Ajé ni àwọn Ẹ̀gbá ń mú ṣe nínú ìlú..
wikipedia
yo
Orílẹ̀-èdè àwọn ìpínlẹ̀ ààbọ̀ka tún ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ agbègbè ní Karisáyè àti pàsífìkí.pẹ̀lú 3.79 ẹgbẹgbẹ̀rún ìlọ́poméjì máìlì (9.83 million km) àti iye tó ju 309 ẹgbẹgbẹ̀rún ènìyàn lọ, àwọn ìpínlẹ̀ ààbọ̀odò jẹ́ orílẹ̀-èdè tótóbijùlọ tàbí kẹrin bíi àpapọ̀ iye ààlà, àti ìkẹta tótóbijùlọ bíi ààlà ilẹ̀ àti bí àwọn olùgbé..
wikipedia
yo
Okòwò àwọn ìpínlẹ̀ odòmẹyà ni okòwò orílẹ̀-èdè tó tóbijùlọ lágbàyé, pẹ̀lú ìdíye under 2009 tó jẹ́ $14.3 ẹgbẹgbẹ̀kẹta (ìdámẹ́rin under olórúkọ lágbàyé àti ìdámárùn ní Àgbáyé ìpín agbára ìrajà wò ènìyàn abínibí tí wọ́n wá láti Asia ti bùdó sí orí ibi tí orílẹ̀-èdè àwọn ìpínlẹ̀ wíwà wà lónì fún ẹgbẹ̀rún lọ́pọ̀ ọdún..
wikipedia
yo
Orilẹ-ede awọn ipinlẹ aṣálẹ̀ka jẹ didasilẹ̀ latọwọ awọn ileàmúsìn mẹtala ti Britani to bùdó si ẹgbẹ́ Okun Atlantiki..
wikipedia
yo
Ilana-ìbágbépọ̀ ilẹ̀ àwọn ìpínlẹ̀ Kaani lọ́wọ́lọ́wọ́ jẹ́ gbígbà bí òfin ní ọjọ́ 17 Oṣù Kẹ̀sán, 1787; Olùwobọ́sí ní ọdún tó tẹ̀lé sọ àwọn ìpínlẹ̀ di apá orílẹ̀-èdè Olómìnira kan ná pẹ̀lú ìjọba àpapọ̀ tó lágbára..
wikipedia
yo
Ni orundun 19th, awon ipinle Niil gba ile lowo France, Spain, Ilẹ̀ọba acetyl, Mexico, ati Rọ́ṣíà, o si Ṣefamora ile olominira Kikus ati ile olominira Hawaii..
wikipedia
yo
Bakanna Etiodo mo Atlantiki, Pasimofìkí ati ìkún-omi Meṣíkọ̀ na tun ni iye apapọ to to 19,9km orikm.Ààlà ori ilẹ je 9,161, km pẹlu ààlà ori omi to to Adam, gbogbokm, gbogbo ààlà ilẹ ilẹ̀ Amẹ́ríkà je 9.8 ẹgbẹgbẹ̀rún km.13-ama re-guusu lati Bode Mo Kanada ati Bode Mo Mebara Jels je 2,500 tte ila-ọrun-iwoorun lati eti okun Atlantiki de p pokeki je 4,500..
wikipedia
yo
Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà dùbúlẹ̀ sí àrin ìlàgbolọ́jọ́ àparíú 24 àti 49 àti larin ìlànináro apáòrùn 68th àti 125, bẹ síni ó pín sí àkókò ilèrìn mẹrin.ÌDÁ àti ÌwóIlẹ̀ Arin Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà ní Ilafiwó tó yàtọ̀ pàtó..
wikipedia
yo
Ó ní ọ̀pọ̀ ilé gbígbé àti ilé koríko.Ojúọjọ́ Ojúọjọ́ dúró lórí ibùdó..
wikipedia
yo
Gbogbo eniyan tí a ti rì bọ omi yẹ kí á wẹ ẹsẹ̀ rẹ̀ ní orúkọ Jesu Kristi..
wikipedia
yo
Our ìgbà tí wọ́n ti fi jẹ ẹ́, ni wọ́n ti ń pè é ní baba-oníbaba, tí wọ́n sì ń pe ilé ẹ jẹ ní ilé baba-mọyì..
wikipedia
yo
Wọ́n ma ń pe igbó yìí ní Igbó-isà ṣùgbọ́n nígbà tí wọ́n kọ́ ilẹ̀ ibẹ̀, wọ́n wá ń pe ibẹ̀ ní àdúgbò ìàṣewó..
wikipedia
yo
Nígbà tí, ó wà láyé, Bbọ̀boko ni wọ́n ma ń pè é, lẹ́hìn tí ó kú tán, ni wọ́n bá ń pe àdúgbò yìí ní bábùkó..
wikipedia
yo
bẹgbé ní orúkọ jẹ́ tẹ́lẹ̀ ṣùgbọ́n nígbà tí ó di wí pé, ẹnì kan tí ó tip ẹ̀ lẹ́nu iṣẹ́-ọba ní ìpínlẹ̀ Èkó tí ó jẹ́ ọmọ ìlú yìí kú, ni wọ́n bá ń fi orúkọ rẹ̀ pe àdúgbò yí nítorí pé, ó jẹ́ ọmọ bíbí àdúgbò yí bákan náà..
wikipedia
yo
Iya rẹ ku ní ọdún 1958, baba rẹ sin ku bákan náà ní ọdún 1959.Igba Ewe rẹwọn bí Olusegun Obasanjo ní ọjọ́ kaàrún, oṣu kẹta, ọdún mẹ́tàloSVwa (1937) fún Amos Ọbalúayé Bankole àti Àṣàyi lílù ìbògún ọ̀lagún..
wikipedia
yo
Olóyè Ọbásanjọ́ jẹ́ ọ̀gágun tó tifẹ̀yìntì kúrò nínú iṣẹ́ ológun ilẹ̀ Nàìjíríà àti olóṣèlú ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Tí àwọn àgbàlagbà ní abúlé pàápàá àwọn ọkunrin bá jẹun tán wọn á “tàtaré”sí abẹ́ igi yìí láti lọ gba atẹ́gùn, ibi tí wọ́n bá ti ń tayò, tí wọn ń “Ta sọ” wọn á wà níbẹ̀ fún ìgbà pípẹ́..
wikipedia
yo
Ti àwọn ènìyàn tí kò mọ ohun tí ó n ṣẹlẹ̀ tẹ́lẹ̀ bá ti ń rí àwọn jagunjagun tí wọ́n ń dé sí ìkìn yìí, wọ́n á ní àwọn ológun ti dé sí ikìn wọn..
wikipedia
yo
Níbẹ̀ ni ilé ìpàdé wọn wà, kí o tó di pé wọ́n tẹ ibẹ̀ dó..
wikipedia
yo
Ní ayé àtijọ́, ẹni tí ó bá kọ́ iṣẹ́-Ifá, tí ó tó àkókò lati ni Odù-Ifá, ilé tàbi àdúgbò yi ni wọ́n máa ń lò lati gba Odù-Ifá náà..
wikipedia
yo
Ìbàdàn jẹ́ olú-ìlú ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ni orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ibadan bere gege bi Ipinle Jagunjagun ti o si wa bee titi di odun kewaa ti o gbeyin China kokandinlogun.Ní ọdún 1893, Ibadan di ilu Amọ̀nà/Ìlú tí ó wà lábẹ́ ase biritéènì leyin ti FI47 tí ó je Báálẹ ìlú Ìbàdàn fi ọwọ́ sí ìwé Àdéhùn pẹ̀lú ẹni tí ó ń se ise gómìnà ìlú Amọna George C..
wikipedia
yo
ìsọ̀rí ọ̀rọ̀ mẹjọ yìí ni wọ́n sì pín sí OLUWA ati kókó gbolohun..
wikipedia
yo
Ìyẹn nipé ẹ̀ àwa yóò ya ìsọ̀rí-ọ̀rọ̀ àti ìṣe ti ìsọ̀rí yìí ń ṣe sọ́tọ̀ sí ara wọn..
wikipedia
yo
Ohun tí ó fà á tí a ó fi mú gírámà yìí lọ nip é ó gbìyànjú láti ṣàlàyé ìmọ̀ abínibí elédè nípa èdè rẹ̀..
wikipedia
yo
Gírámà yìí ṣàlàyé gbólóhùn píńnà, gbólóhùn tí ó jẹ àdàpè ara wọn abbl..
wikipedia
yo
Ohun ti àmì ọfà yìí n sọ ni pé kí á tún gbólóhùn (gb) kọ́ ni àpòr àti Apii..S..
wikipedia
yo
A ò mẹ́nu ba àfòmọ́ dáadáa ní iwájú ṣùgbọ́n kí a tó ṣe èyí, ẹ jẹ́ kí á sọ̀rọ̀ nípa àpòr àti Apis..
wikipedia
yo
Òdòdóawo ń òdòdó die 1korotin 2akalifa 3ila abilà 4alamàǹdà 5kerebùjẹ 6Mari 7pinibùsùn 8róòsì Obruyi 10bo-rin-òdòdó11 12okan 13yun-únyún14igba ilé 15 (Ido 16ọrọ̀ agogo/ọrọ adẹ́tẹ̀..
wikipedia
yo
Adebayo Akande Fálétí (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n Oṣù kejìlá 1930) jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, AKÉWÌ , olùkọ̀tàn, àti eléré orí-ìtàgé, bákan náà ní ó tún jẹ́ Ongbugbu èdè Gẹ̀ẹ́sì sí èdè Yorùbá, ó sin tún jẹ́ omi orí ọdún ẹ̀ro-Ma-ìtàn Radio, olóòtú ètò orí orí ọdún TV, àti olùdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán àkọ́kọ́ ní ilẹ̀ Adugbọ̀n Áfíríkà tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Western Nigeria Television (W| Fálétí náà ló ṣe ògbufọ̀ orin ÀMÚYẸ ORÍLẸ̀-èdè Naig National Anthem láti èdè Gẹ̀ẹ́sì sí èdè abí Yorùbá..
wikipedia
yo
Bákan náà ni ó tún ṣe ongbugbu fún ohun ti Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nígbà kan rí lásìkò ológun, ìyẹn Ibrahim Babangida so, pẹ̀lú ti Ààrẹ-fìdí nígbà ayé ológun kan rí Chief Ernest Shoneka, nípa lílo èdè Yorùbá tó gbámúṣé..
wikipedia
yo
Fgbọ́rọ̀ ti tẹ̀ ìwé-atúmọ̀ èdè Dictionary Yorùbá ní èyí tí ó ní àbùdá ògidì Yorùbá nínú..
wikipedia
yo
Ìfẹ́ sí ìlú ìpínlẹ̀ Èkó jẹ́ kìlómítà igba ó lé mejidinlogun (218) tí àwọn tí wọ́n jẹ́ olùgbé ibẹ̀ lápapọ̀ jẹ́ 509,Iṣifi níye.Gẹ́gẹ́ bí ìtàn ṣe sọ, Ilé-Ifẹ̀ ni wọ́n dá sílẹ̀ pẹ̀lú àṣẹ Olódùmarè nígbà tí ó pàṣẹ fún Ọbàtálá kí ó wá láti dá ayé kí ilẹ̀ sì bẹ̀rẹ̀ sí ń fẹ́ láti ibẹ̀ lọ káàkiri àgbáyé; Ìdí nìyí tí wọ́n fi ń pe Ilé-Ifẹ̀ ní Ifẹ̀ òòyẹ̀, ibi ojúmọ́ ti ń mọ́ wáyé..
wikipedia
yo
Àmọ́, Ifẹ̀ yí ni Ọbàtálá pàdánù rẹ̀ ṣòwò Odùduwà àtẹ̀wọ̀nrọ, èyí ni ó fàá tí fàá ká jà ṣe wà láàrín àwọn méjèèjì..
wikipedia
yo
Bákan náà ni ilẹ̀-Ifẹ̀ ní ọ̀kanlélúgba òrìṣà ti wọ́n ma ń bọ ni ọjọ́ kọ̀ọ̀kan yípo ọdún..
wikipedia
yo
Ẹni kan sọ pé sán-ányán ni aṣọ tí ó wọ̀ níwọ̀n ìgbà tí ó ti jẹ́ pé àwọn ọmọdé kìí tètè gbàgbé nnkan, Akin Olúṣínà ní kí awọ́n bèèrè ìbéèrè nípá Fáwọlé lówó Fólúkẹ́ àti Bándélé..
wikipedia
yo
Ó ní kí ti òun má baà jẹ́ òfo nílé Orímóògùnjẹ́ ni ó jẹ́ kí òun jí owó rẹ̀ gbé..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí ó jiyán tán ní ilẹ̀ olóúnjẹ yìí, ó mu ìgò otí kan àti àbọ̀ nínú ọtí tí Akin Olúṣínà rà..
wikipedia
yo
Ní orí kẹta àkòlà yìí ni a ti ṣàwọ́ nípa ìgbéní fonọ́lọ́jì tí ó wà nínú ẹ̀ka-èdè iṣẹ́-Èkìtì..
wikipedia
yo
ÀGBÁLỌGBÁBỌ̀ Iṣẹ yii da le awọn tuntun ti o jade ninu iwadii ti a se a si tọka si awon ibi ti a lero pe iṣẹ ku si.M.G..
wikipedia
yo
Ìtàn sọ fún wa pé, èpè, ní ẹ̀bá ìlú Òndó ni ó kọ́kọ́ fi ṣe ibùgbé lẹ́yìn tí wọ́n kúrò ní Ilé-Ifẹ̀..
wikipedia
yo
Alakúnrẹ wá ja owó rẹ ninu ìrọ́kẹ̀kẹ̀ ati akitiyan lati jẹ ọba fún ilú Àkúrẹ́ bi ó tilẹ̀ jẹ́ pé òun gan-an ni ẹni kìíní ti ó kọ́kọ́ tẹ ilú Àkúrẹ́ dó..
wikipedia
yo
Ó gbé adé kan lọ́wọ́, ó súre fún ajápadà, ó sì sọ fún ajápadà pé, ‘Mo fi adé yìí jí o’ mo fi adé jí ọ, ni ó wà di ‘Deji’tí ó jẹ́ orúkọ oyè ọba ilú Àkúrẹ́, gẹ́gẹ́ bi ẹni ti Odùduwà fi adé jí
wikipedia
yo
A ri igbó pé obìnrin méjì ni ó wà nínú wọn.3 Obìnrin kìíní ni ẹyẹ – arọ tí ó jẹ ọba ní ọdún 1393 títí di ọdún 1419 A.D..
wikipedia
yo
Ohun tí ó fà á tí òye fi kan obìnrin yìí nipé ẹ, òun nìkan ni ìfà rẹ̀ fọ́ rere láàrín àwọn tí wọ́n dárúkọ fún ifá rẹ̀ fọ́ rere láàrin àwọn tí wọ́n dárúkọ fún ifá..
wikipedia
yo
Ọlọgbín ti fi lọ tẹlẹ̀ pé òun yóo ṣe ẹ̀yẹ ikẹhin fún bàbá òun tí ó ti kú nítorí náà nígbà tí wọ́n rí aláràn-án orí ninú aṣọ òdòdó, wọ́n ṣe bí ológbín tí ó ti kú ni, pàápàá tí abàmì ọmọ tí ó pọ́n dà bí ike ẹ̀hìn rẹ̀..
wikipedia
yo
Ṣób-wà yìí ni ó ṣì di alágbàá (Bàbá màrìwò) títí di òní olónìí..
wikipedia
yo
Àwọn mìíràn le ṣe àtìpó níbẹ̀ fún ìgbà díẹ̀ kí wọn ó sì padà sílé nígbà tí wọ́n bá ti ra ara..
wikipedia
yo
Òun ni ọ̀kan nínú àwọn ewì `tí a máa ń fi ń yin ẹnikẹ́ni tí a bá ń sun ún fún yálà ní ìgbà tí ó bá ń ṣe ìnáwó tàbí àríyá kan..
wikipedia
yo
Bí ó ti jẹ́ ohun tí a fi ń yin eniyan náà ni ó tún jẹ́ ohun tí a lè fi pe akiyesi eniyan sí ìwà àléébù tí ó ń hù..
wikipedia
yo
Ju gbogbo rẹ̀ lọ, ibi tí a bá gbé ń ṣe nǹkan tí ó le mú ìdùnnú lọ́wọ́, yálà ilé sisí ni tàbí ìwúyè ni a tí ì máa ń rí àwọn àsunrárá..
wikipedia
yo
Nínú ọdún Iléyá tí àwọn Mùsùlùmí tàbí ọdún ún Kérésìmesì ti àwọn onígbàgbọ́, àwọn Onirárà a máa káàkiri ilẹ̀ àwọn ẹlẹ́sìn wọ̀nyí, láti kí wọn kú ọdún nípa rárá sísun..
wikipedia
yo
Èkíní ní ohun pàtàkì ni a ń bá pàdé nínú èrè Apii..Ìrì..
wikipedia
yo
Eré yìí sábà máa n ní olórí tí yio máa dá orin, tí àwọn kòtò yio máa gbé tí ìlú bá ń lọ lọ́wọ́..
wikipedia
yo
Nígbà míràn, ó lè ṣe ẹni tí n dá orín náà ni yíò máa ṣbáwọn láàrín ẹrẹ̀, ó sì tún lè jẹ́ ènìyàn méjì yàtọ̀ sí àwọn tí ń dárin..
wikipedia
yo
Wọ́n a máa jó, wọ́n a sì máa pa àtẹ́wọ́ tí òmíràn bá ti wọ̀ wọ́n lára..
wikipedia
yo
Kò sí bátànì kan pàtó tí alajúhan gbọdọ̀ tẹ̀lé ninu eré nítorí pé bí ó bá ṣe wuni ni a ṣe ń ṣemọ́lé ẹni ní àpẹẹrẹ ìsàlẹ̀ yìí, alámọ̀ ni eléré Apiìrì yìí fi bẹ̀rẹ̀ erèé rẹ̀..
wikipedia
yo
Láti ọmọmmún ni ìyá Ajíbógun Ọwá Iléṣà ti kú Ìyá Agígírì tí ó jẹ́ ẹ̀gbọ́n ìyá rẹ̀ ló wò ó dàgbà, Òban rẹ̀ ló sì mún dàgbà..
wikipedia
yo
“Ọmọ àlè ní í rínú tí kì í bí, ọmọ àlè la ń bẹ̀ tí kì í gbọ́” báyìí ló gba ìpè (ẹ̀bẹ̀) baba rẹ̀..
wikipedia
yo
pẹ̀lú ìṣẹ́gun lórí àwọn arákùnrin rẹ̀ yìí, kò ní ìtẹ́lọ́rùn, òun náà fẹ́ ní ibùjókòó tí yóò ti máa ṣe ìjọba tirẹ̀..
wikipedia
yo
Ní ìlú náà ẹrẹ̀ ṣe ìdíwọ́ fún àwọn jagunjagun Ọ̀yọ́ ni wọ́n bá fi ń pe ìlú náà ni Ìjẹ̀bú - Ẹrẹ̀..
wikipedia
yo
Nígbà tí ọba ìgbàbí -Jẹ̀ṣà bá ń bộ wáyìn òhìn ọ̀pọ̀ èbí tí ó ti lọ ní Ileṣa fún ọdún ogun, Ọtáforíjọ̀ ni àwọn ènìyàn rẹ̀ ti gbọ́dọ̀ pàdé rẹ̀..
wikipedia
yo
Ara Ìwàrẹ̀fà mẹ́fà ni Ògbóni méjèèjì yí a ní Iléṣà ṣùgbọ́n ògbóni Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà ni aṣáájú àwọn Ìwàrẹ̀fà náà..
wikipedia
yo
Fún àpẹẹrẹ Ilé - Ẹ̀kọ́ gíga (Grammar Schoo) méji ti ó wà ni ilú náà, òógùn ojú wọn ni wọ́n fi kọ́ wọn, bẹ́ẹ̀ náà ni Modern School wọn..
wikipedia
yo
Ọdún 1845 ni ọba abẹ́wèé rán ologbenlánlá àti àwọn ọmọ ogun rẹ̀ ló jẹ́ ìpè ọba ọ̀sẹ̀mọ̀wé ti Òǹdó2 wọ́n sí tẹ̀dó sí òkè-Ìgbò..
wikipedia
yo
Gbogbo aáyan àwọn ìfẹ́ láti mú kí ologbeńlá padà sí Ifẹ̀ lẹ́yìn tí ó ti ṣẹ́gun ní Òǹdó ló já sí pàbó..
wikipedia
yo
Oko-àrójẹ àwọn Òndó ní òkè-igbó kí o tó Dikùn ẹ́ ọlọ́gbẹ́ńlá àti àwọn ọmọ ogun rẹ̀ fi ibẹ̀ ṣe ibùjókòó wọn..4..
wikipedia
yo
Bákan náà ni àwọn ìfẹ́ ń fẹ́ kí àwọn eniyan rẹ tí ó wà ní òkè-igbó san owó-orí wọn sí àpò ìjọba ìbílẹ̀ ìfẹ́ nítorí pé ìfẹ́ ni wọ́n1..
wikipedia
yo
Nígbà tí ṣbáṣlẹ̀ Ojo wà ní "Radio Nigeria" kí ó tó lọ sí "Western Nigerian Television Station (WNTV)" ni wọ́n ti kọ́kọ́ ran àwọn onímọ̀ ibẹ̀ lọ sí ilé ẹ̀kọ́ láti lọ kọ́ ẹ̀kọ́ nípa bí wọ́n ṣe ń ṣiṣẹ́ ní iṣẹ́ iṣẹ́ redio..
wikipedia
yo
Fun imo riri eto ti o n se ni ori 'Television Broadcasting Co-operation Oyo State (bcos) so dáa dáa tí àwọn ènìyàn ń jẹ́ anfaani rẹ̀, aláyélúwà ọba Oba Emmanuel Adegboyega Adeàdéhùn Oiku 1..
wikipedia
yo
Ní ilẹ̀ Yorùbá pàápàá jù lọ “South West”, oun ni ó bệrệ rè, kọ́ sí ilé iṣé redio tí ó síwájú rẹ bệrệ ètò yìí “phone in” èyí ara.a.O..
wikipedia
yo
Adéoyè (2000), 'Ìtàn Ìgbésí ayé bámijí Ofe', láti inú atupẹlẹ Iwe Oba Adikuta ti bamiji Ojo Kozion Aroko fún oye Biee, Dall, OAU, Ifẹ Nigeria.Àwọn ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Fún àpẹẹrẹ, ọmọ ìlú irun, àfin, ẹsẹ̀ àti ìró tí wọ́n wà ni agbègbè kan náà pẹ̀lú ọgbàgi lè sọ tàbí gbọ́ èdè ọgbàgi pẹ̀lú ìrọ̀rùn..
wikipedia
yo
Adulójú (1981), ‘Ìlú Ogi', Láti Inú ’Ọdún Òrìṣà Òkè Ogi ní Ìlú Ogi Akoko', Àpilẹ̀kọ fún Oyè Bíee, Dall Ód Oodua, Ifẹ̀, ojú-ìwé 1-Àwọn..
wikipedia
yo
Àwọn ògbógi olórí ogun nígbà náà ni ‘Ẹkìn ajagunmo àti ẹnikò lmọ̀dí ti òkè-ọ̀pọ̀ àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ológun mìíràn..
wikipedia
yo
Ní àkókò tí mò ń kọ ìwé yìí, ìlú méjì ló papò tí a ń pè ní Ọ̀rá-Ìgbómìnà - Ọ̀rá àti Òkèẹ̀wù, ìlú ọlọ́ba sin i méjèèjì..
wikipedia
yo
Èékìn ajagun-má-dín ló wa yára yí gbogbo ìlú ọ̀rá po..
wikipedia
yo
Ẹnikótún lànífẹ̀ẹ́ lọ lé ogún Èkìtì-parapọ̀ títí dé ọ̀dọ̀ kan tí wọ́n ń pè ní Arigbara..
wikipedia
yo
Akesin ba àwọn ìjòyẹ̀ rẹ̀ sọ òrò náà, wọn sì gbà..
wikipedia
yo
Ìran lagbodi ọmọ òpómúléró tó wá láti ilẹ̀ Alapinni ní Ọ̀yọ́ ilẹ̀ ni ìyáàfin bojúwòye ìran ẹnifọ́n sì ní ìyáagbà dẹńlé..
wikipedia
yo
Bàbá mi wá ṣàlàyé pé aláfà bàbà tí òun pa á nítàn pé àwọn òkèwú tọrọ ilẹ̀ lọ́wọ́ ọ̀rá, ọ̀rá sì fún wọn láàyè lórí ilẹ̀ àwọn ìjàṢiọ àti òkè àkànan..
wikipedia
yo
Ibi ti igi náà wà nígbà náà ni à ń pé ní arárómi lónìí..
wikipedia
yo
Oun ni o jẹ ẹni akọkọ ti o jẹ oye Awujale - 'A-mu-ija-iledinlógúnèyí ni ẹni ti o pari ija ti o ba nílé..
wikipedia
yo
Nígbà tí wọ́n lọ bi ìfà wó, Ifá ni kí wọ́n máa bọ Ọbàtálá ní ìdílé náà, láti ìgbà náà lọ ni wọ́n ti ń bọ Ọbàtálá ní ìdílé yìí..
wikipedia
yo
Tí ó bad i àsìkò ọdún òrìṣà yìí, àríyá ni fún gbogbo àwọn ọmọ àdúgbò yìí àti fún ìlú pàápàá.Àwọn ìtọ́ka sí C.O..
wikipedia
yo
Onanuga (1981), 'Ilu Ijebu-Ode', lati inu 'odun orisa agẹmọ ni agbegbe Ijebu-Odeèdè apileko fun oye BiEE, Dall..
wikipedia
yo
OAU, Ifẹ̀, Nigeria, ojú-ìwé 3-6YORÙ ìlú àti abúlé ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Black;adj; (The Black Dog is here.) duduAjá dúdú náà wà níbí..
wikipedia
yo
Èso títà ni ọwọ́ mi fi mí sílẹ̀, gbájú mọ́ ohun tó kàn ọ́..
wikipedia
yo
It is short end from “Tokabu" gbére; -irúfẹ́ èso igi kan ò jẹ́ gbére..
wikipedia
yo
Ìyàwó Ògúnlọlá jẹ́ baba Ìjèṣà kan ní ọwọ́, níbi tí wọ́n ti jọ ń sọ̀rọ̀ lọ́wọ́ ní sóun Ògúnlọlá wọlé, èdè àìyedè dé láàrin Ògúnlọlá àti baba náà, sóun sì lu baba náà pa..
wikipedia
yo
Ògúnlọlá bá ẹlẹ́mọ̀ṣọ́ jà ó sì paá ni ó bá gé orí rẹ̀, ó sì gbé fún Aláàfin..
wikipedia
yo
Ọba ìráoṣù ọba kéfàyà Kábíyèsí ọba ọba tótó ọba ìrábó abísí ọba ọba Mo fẹ́ pé n kò ní mu ẹmu ọba ni mo fẹ́ pé n kò mú gorò abẹ́ tógun ralú Mib Ara Ìyọ wíjọ́ Ara lọ́bọ sá l iráìpín n jẹ́ jẹ́. Ọmọ ònìyàn Kóǹkólóyo ọmọ bárì ní ogun Ògùn ọmọ ari Mo lùlù fún Ìebi Láín Lákà Mo gbé òkè Lárù gbé Mo gbélé ṣe bí ọba ọmọ òkè gbélé Ìyá jà tó an Mo kéde kéde ara mú Le mú Ẹsẹ̀ Ẹsẹ̀ ké Ọ̀kan ti yí lulẹ̀ ó kú ọ̀kan ọmọ ọlọ́rọ̀ kan ọ̀rọ̀ kan Èyí ti fà lọ́gànjọ́ yányán ilé wọn kò gbọdọ̀ ṣòwò odò Odò Èyí ni àlọ́gi kan ni àlọ Mo gbọdọ̀ sárá ògì sára ọmọ kékèké ilé wọn ó gbọdọ̀ sunkún èyí tí ó bá sunkún mọ́ lọ̀rọ̀ ni yóò mo gbé lọ gbé.. Lọ gbé lọ Mo gbé Mo gbélé Mo Mo gbélé Mo l
wikipedia
yo
Ọmọ òkè kékèké ni Násì Òkunwọn yí láyé.Abẹ tógun rálú ọmọ ara sùnú tẹni wíjọ́ Ìjẹ̀ṣà kò rídìí iṣanàìlè lòní Ọwá ti mú iná roko abẹ tógun ra ọmọ ara lỌṣìn.Mo tún yí yún tí kẹ̀dẹ̀ngbé yìn mo tún lọ rè dé òkè àgbò..
wikipedia
yo
Ọba tótó mọ lèmi kò perí ọba ọba wọn ń perí ẹ̀ ni ṣòkòtò ọba ni wọ́n ń perí rẹ̀ ní sábàra ọba ni wọ́n ń perí rẹ̀ nílé Iraoṣù ọba olókùn ẹṣin ara ilé mi àbí irú ẹṣin mi tíèmiá gbún ẹṣin ní kẹ́ṣẹ́ a lọ mọ jọ ẹ̀dọ̀kó gbogbo ara ẹ̀sìn wọn wá kọ́nà ṣáṣá ọba kòle tí ń retí ẹni tí yóò tẹ́ fún.Ọba ń náà ní í bẹ lọ́nà ti òkè àgbò.Abẹ tógun rálú ọmọ ara lỌṣìn tẹ́nì wíjọ́ ara lọ́dọ̀ kankan lọ́mọ olóyè nílé ọmọ olóyè lóde.Òye náà wọn kò ní parẹ́ mọ́ yín lọ́wọ́.Orí àpẹrẹ yóò gbé yín Èèyàn bàbá ẹ̀yìn èyí tó ń bẹ níbẹ̀ wọn kò ní kú mọ́ yín lọ́wọ́ tótọ́ ààtọ̀ gb mọ́ lémi kò perí ọba ọba ní ń bẹ lọ́nà ti Ìjẹ̀ṣà abẹ́ Ìjẹ̀ṣà abẹ́ tógun ra ọmọ ara dári tẹ́ni wíjọ́ ara lọ́dọ̀ kankan..
wikipedia
yo
Ẹ wòó nílé ọlọ́rọ̀ nÌjèṣà abẹ́.A rílẹwọ ní mókun.A dínà kirimi ní Ìjèṣà.Láì jẹ mo rọ múmù..
wikipedia
yo
Láì ro Morońkọlà.A bí bàbá jẹ ọba á bílẹ̀ oníga lẹ́yìn.Alamu ọ̀kín..
wikipedia
yo
A bílẹ̀ gbága láàrin.Ọjọ́ ọjọ́ kan ò dùn.Ní ọjọ́ a fẹ́ yan ọmọ oyè ní Òṣogbo.Gbogbo ọmọ ọba dúró gẹ́gẹ́ bí ogún.Jagun Akinṣọ̀wọ́n di aláf ti.Iyì Moromónì.A bi Baba jọba.Akọgun Òṣogbo Àgbàlagbà Oyè ọmọ Fọláṣọdẹ là.1.Lẹ́yìn Ọba Moroka.A bí baba j'ọba.Osa Àkàndé làláti Ọba..
wikipedia
yo
Moroka A bí bàbá J'ọba ìyálóde làọ̀gún .Ọmọ Adélé.N náà lọ _ Ọba.Moroka a bí bàbá J'ọba.àti Àwo àti ọ̀ríríbíà.Wọn ó tètè mọ̀ pé.Jagun Akinṣọ̀wọ́n sòtítọ́.pé làpàdé kan kan.Ọmọ Alade. Oroko J'ọ́ ìlú Tọ́rọ̀ kin Kin.
wikipedia
yo
Agbùrùwa fuo.Bàbá Olùgbèjà. Ele baba oyin da.Ọla Aláyélúwà j'ọba káyé ò leè rọ́jú.O joyè lógún ọmọ ọba.Ó joyè tán fara ẹ̀ mọ́dọara.Ara Niu gbé ní.Ẹgbàá ò gbé níàtẹ́lẹwọ́. Kì í pẹ́ lajòbí mátan n fọ́ dé sọ́kàn.Bàbá bẹ́ẹ̀ni ni kó yàrá ẹ̀ lọ́tọ̀ o.Ọ̀dẹ̀ gbà kò ṣe dáa sí Ìlú. Ìlú kan díẹ̀-lójú òde. Ọmọ ṣẹlẹ̀ ọkọ ọ̀hún ẹ̀ dán. Ara ẹ̀ oko ọ̀kè ẹ̀ dán..
wikipedia
yo