cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Bí Asghar Hussain ṣe pé ọmọ ọdún mẹ́ta dín lógún sí méjì dín logun tíó dé iyàrá ìkàwé Arabic ní dàrúl Ubáàd Deọand, bàbá rè jáde láyé ní ògún jọ oṣù kẹsàn ọdún 1894..
wikipedia
yo
O da enu duro ninu eko re fun bi odun kan o tesiwaju lati ko awon omo le ko ni odo awon baba nla e Madrasa.Ni ibeere awon mahmud HH deobandi, asghar Hussain wo ile eko darul UIbùdó Deoband Lekan si ni ojo kini osu kerin odun 1896 osu tesiwaju ninu iyara ikeko Arabic..
wikipedia
yo
Ọkọ nípa Sahih Al-Bukhari, Sahih Muslim, já` AT-tir-hi àtisùnan Abu Daléod pẹ̀lú Mámud HH Debandi..
wikipedia
yo
Awon oluko re to ni Azizur Rahman USmani ati Ghulam raṣọọ BaGHwi..
wikipedia
yo
Ọkọ ẹkọ gboye ni 1320 Ah osi gba ami ikẹkọ gboye ni owo Mahmud HH deobandi ati Hafiz Muhammad Ahmad.O gba ase ọmọ leyin ti imdatso Mujirus Makkí ninu ẹka Chihuhu ti tawwúf.Iṣẹ leyin eko rẹ ni darul Ubáà Deoband, osi se gege bi osise ni darul U139 ko ja odun kan..
wikipedia
yo
Àwọn olùkọ́ rẹ̀ mahmud Ḥasan deobandi àti Hafiz Muhammad Ahmad ran ló sì Madrasa ti atala masjid, Jamunpur fún ipò olùkó àgbà òṣì ṣíṣe fún ọdún méje..
wikipedia
yo
Ní àwọn àkókò ní ọdún 1327 Ah, òfin òkúta ilé MadraSatul iṣlah le ilé ni Sarai Meer, Azamòfuurufú ní 1908.A sì dàrúl Ujíjẹrà Deoband asì fún ní ipò alátúnṣe pẹ̀lú àwọn tó ń ṣe àtún ṣe sí Journal Al-Qasim ti dàrúl UbáàSabadi, tí alátúnṣe nã sì jẹ́ wítúnlànà Hbee Rahman..
wikipedia
yo
afun ni ipo olukọ ti sunan Abu Dawud ni Daakokol Ubáà Deoband otun ko awon akeko ni iwe Tafsir ati fiqh Like Yemil ati Durr-E-A-Aratar..
wikipedia
yo
His Notable Students include Muhammad Shafi Dobandi, manazir Ahsan gilani..
wikipedia
yo
Ótún Madrasa àwọn bàbá ńlá rẹ̀ ṣe ti àti parí láti ìgbà ikú bàbá rẹ̀..
wikipedia
yo
Madrasa padà wà lálà ìsó ọmọ kèfèrí rẹ̀ Sayd Bilad Hussain Mianan (an..
wikipedia
yo
Wọ́n ní ọmọkunrin meji, tí ń ṣe Sayyíd orídtar Hussain ati mian bìlàl Hussain, ati ọmọ obinrin kan, Feìlọ́poẹ̀dá..
wikipedia
yo
Fìṣòroọ òkú lẹ́yìn ọdún mẹ́jọ tí ó ṣe ìgbéyàwó, ọmọ rẹ̀ ọkùnrin sì gbẹ̀yìn rẹ̀ Syed Farhat Hussain ti oní àjọ sepo pẹ̀lú HamÒní DlúHánà ní Karachi..
wikipedia
yo
Ọmọkùnrin Hussain's tí njẹ́ Sayyíd oríd Hussain jẹ́ olùkọ́ Hadith ní Dayal Ubáàd Deriand, ọ̀sìn ní Oṣeré ṣeminarí
wikipedia
yo
Hussain's àti àwọn ọmọkùnrin ẹ̀mí Sayyíd bìlàl Hussain ọmọkùnrin mẹ́ta tí nṣe , Sayyíd jámeel Hussain, Sayyíd Khalẹ̀el Hussain, and Sayyíd jálẹ̀el Hussain sì gbẹ̀yìn wọn; àti ọmọbìnrin méjì tí nṣe, Ogdá Khatún àti àábí Khatun.Ikú Àìsàn ọ̀kan pa mían Asghar Hussain ní ọjọ́ kẹjọ oṣù kíní ọdún 1945 (22 Muharram 13 Ah64).Wọ́n sì sin sí rander, Surat.See also List of Students of mah HH DHofed list of deband-sherọ 20sí..
wikipedia
yo
Ìṣílọ àti àyípadà lórí ayika àgbáyé jẹ́ iwadi nípa ipa tí àyípadà ojú ọjọ́ kó nínú lọjin ọmọ ènìyàn àti ìṣípt ni wọ́n tẹ̀ sí ta ní ọdún 2011..
wikipedia
yo
ìwádí yìí wá láti ẹ̀ka ẹ̀rọ ní abẹ́ àkóso ìjọba UK tó dá lórí ìmọ̀ ìjìnlẹ̀.Èyí ni wọ́n pè ní èrò ìròyìn lãrín àwọn tí òun ṣiṣẹ́ ní abẹ́ ojú ọjọ́ àti lósún..
wikipedia
yo
Ìròyìn ni Ọ̀jọ̀gbọ́n Richard Black ti ilé ìwé gíga Sussex ṣájú rẹ̀..
wikipedia
yo
Iwadi fi ọwọ si àyọkà lori isilo ati ayipada ojú ọjọ́..
wikipedia
yo
Iwadi yii fi ìgbéròyìn jade lori gbigbe jade rẹ.iwadi yi da lori ẹrọ ti wọn dè mọlẹ̀..
wikipedia
yo
Ìròyìn ṣọpẹ́ LÁTARA ÀYÍPADÀ OJÚ ỌJỌ́ ÀWỌN ÈNÌYÀN NI LÁTI DÚRÓ SÍBI TÍ WỌ́N WÁ..
wikipedia
yo
ìwádí fi ìdí ẹ̀ mọ́lẹ̀ pé èyí jẹ́ kí àwọn ènìyàn di tálákà látàrí ìbàjẹ́ ilẹ̀..
wikipedia
yo
Ìròyìn yìí jẹ́ kó gbajúmọ̀ pé lólọ ní aṣamudọgba fún àyípadà ojú ọjọ́..
wikipedia
yo
Awon Olukọwe Litireso Sope Lolo je ọna kan gbóted ti awon eniyan maa farada ipa ti ayipada oju ojo ko ni isilo.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Orías Zuchi (ọjọ́ìbí March 27, 1970) jẹ́ òṣèré ará Italia.Mografy plaọláńlá (1989), Dir..
wikipedia
yo
Marcello Cẹ̀ṣẹ́ná Fermo pọ̀sta Tinto brass (1995), Dir..
wikipedia
yo
Kotsandro di rọ̀bilant Carroelle Felici (2003) (Short), Dir..
wikipedia
yo
Štefanọ Calvarängnä come un Fiore (2023) (Short), Dir..
wikipedia
yo
GianLuca Ansanel)?”ata La Crisi del Teatro (1994), Dir..
wikipedia
yo
Luca ronconiiwe La Vicina di FiTamarillilli De Gris Editori, Npoli, Italy.Ìtọ́kasí.web Official websiteawọn oṣere..
wikipedia
yo
Alyh ńnáni jẹ́ òṣèrékùnrin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, olóòtú eku lórí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán, àti òṣìṣẹ́ orí YouTube..
wikipedia
yo
Ó gbajúmọ̀ fún ìga rẹ̀ nínu fíìmù àgbéléwò Banana Island Ghost, èyí tó mú kí wọ́n yàn án fún àmì-ẹ̀yẹ Ayakàn àti ìkẹẹ̀ẹ́dógún ti The Ama Awards fún òṣèrékùnrin tó dára jù, ní ọdún 2018 àti 2019..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2022, ó kópa nínu fíìmù Netflix kan, tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Man of God, ẹ̀dà-ìtàn tó sì ṣe ní Samuel Ọbalọ́lùseìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ Aakah ńnáni wá láti Ìpínlẹ̀ Í, wọ́n sì bi ní January 31, ní Port Harcourt, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, pẹ̀lú àbúrò mẹ́ta..
wikipedia
yo
Baba rẹ̀ jẹ́ òṣìṣẹ́ ní imMigration Office, ìyá rẹ̀ sì jẹ́ oníṣòwò..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé-ìwé Pampers Private School, ní Surulere, fún ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ rẹ̀, ilé-ìwé TopGrade Secondary School ló sì ti kọ́ ẹ̀kọ́ girama, ní Surulere..
wikipedia
yo
Ninu ẹ̀kọ́ Mass Communication lati Covenant University.Àtòjọ àwọn fíìmù rẹèyí ní àtòjọ àwọn fíìmù àgbéléwò ti Aayoh ńnáni kópa nínú.Fíìmù Ori ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán eré orí-ìtàgé-ìjojọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ Bíṣọ́ọ̀bù Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ìlérí ọ̀ladiméjì Alọ́to tí olùgijẹ rẹ̀ ńjẹ́ MohBad tàbí Ìmọ́lẹ̀ ( Wọ́n bíi ní 8 June, 1996 ó dágbére Faye ní 12 September 2023), jẹ́ akọrin Takasu àti òǹkọrin tí òún gbé ní ìlú Èkó..
wikipedia
yo
O ko n gbe orin sita pelu àtìlẹhìn ile ise igb'orin sita ti naira Marley (Marlian Records), o kuro ni abe ile ise yi ni odun 2022..
wikipedia
yo
O gbajugbaja pelu awon orin Àdàkọ re bii "Mopọ̀n", "feel Good" ati "KPK (Ko po ke) ti o gba itọkasi fun ami eye (The Ray) ní odun 2022.OLUWA ni 2016.OLUWA OlaDimeji ni won bi ni Ketu, Nigeria.Iṣẹ Eko.Iṣẹ Orin Orin Moh gbe awo orin ti o pe akole re pe akole ni "Light) (Wori (Ìmọ́lẹ̀), ninu odun 2020, eleyi ni o tele Orin “Mo", ti o ti se papo pelu naira Marley ati Lil K..
wikipedia
yo
MohBad gba Ìtọ́kasí emárùn fún àmì ẹ̀yẹ (The Beatz Awards) ní ọdún 2021.Wo ka MohBad kún àwọn olorin mokanlelogun àkọ́kọ́ (Top 21) lórí ate AudioMack ní ọdún 2021..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2022, MohBad tun ṣe orin tuntun miran lati ọwọ́ Rexxie ti o pe ni "Peace"
wikipedia
yo
O leke téńté tabili eyi (50) Orin Turntable Charts ni ọdun 2021 ati ogorun (100) akoko ni ọdun 2022..
wikipedia
yo
Orin "Peace kanna tun gbégbá orókè lórí à Apple Music Chart Nigeria.MohBad Darapọ̀ mọ́ ilé iṣẹ́ orin "Marlian Records World" ní ọdún 2019 níbi tí ó ti gbé orin "Light jáde orin yí jẹ́ ìpele mẹ́jọ, Davido, naira Marley ati Lilkesh kópa pẹ̀lú Re.Naira Marley ni Alakoso Awo orin naa pẹlu àjọṣepọ̀ ilé iṣẹ́ "S, Rexxie, P.Beat ati Austin Sinister..
wikipedia
yo
Àwo orin "Tralle" ni ó kó ṣe ní June 2023, lọ́pọ̀ tí ó kúrò lábé ilé iṣẹ́ Marlian Records tí ó ṣẹ̀dá ilé iṣẹ́ orin tire tí ó pè ní "ìwà ;
wikipedia
yo
Mel je akojopo orin ọtọtọ mẹjọ ti won gba ogún-iṣẹ lapapọ..
wikipedia
yo
Lára wọn ni ó ti kópa pẹ̀lú Zlatan àti Belbella Shda, lábẹ́ ìṣàkóso Niphra àti tìmí Jay..
wikipedia
yo
Awo naa gbégbá orókè lórí àtẹ apple Music ní Nigeria ní ọ̀sẹ̀ àkọ́kọ́ tí ó jáde, àti ní ọ̀sẹ̀ àkọ́kọ́ tí mohbad jáde Lole-rúhámà-òróró fi òfin gbé Mo Badh ní Feb 2022, Àjọ tí ó gbógun ti lílo egbògi olóró (Nnd/Lea) fi òfin gbé MohBad, Zoleté àti àwọn mẹ́rin míràn ní ilé wọn tí ó wà ní Lekki, Ìpínlẹ̀ Èkó fún níní egbò igi olóró bíi MDMA àti Igbó (2] Ní'káwọ́.Àwọn foon kan lórí ẹ̀rọ ayélujára ṣe àfihàn bí àwọn òṣìṣẹ́ Àjọ tí ó gbógun ti lílo egbògi olóró (FM (FM) ṣe inú ilé àwọn olórin náà tí ó wà ní agbègbè Lekki ní Ìpínlẹ̀ Èkó..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́bí wọn ṣe sọ, àwọn òṣìṣẹ́ àjọ tí ó gbógun ti lílo egbògi olóró (ndLea) fi òfin mú àwọn olórin náà láì ní ìwé àṣẹ fẹjú múni tí wọ́n sì fi ìyà tí ó lowúrà jẹwọn.Àjọ tí ó gbógun ti lílo egbògi olóró (nd) jẹ́rĩ sí ìréde ná láti ẹnu agbẹnusọ wọn wípé lóòtọ́ ni wọ́n bá egbò igi olóró bíi MDMA àti igbó (2] Ní'káwọ́ wọn..
wikipedia
yo
Lẹ́hìn-Ó-rẹ̀hìn wọ́n dá MohBad, Zoleesta àti àwọn mẹ́rin kòlònà sílẹ̀.n-Rọ-ro láàrin MohBad, Naira Marley àti Sammy Larry lẹ́yìn tí MohBad ti lo ọdún méjì pẹ̀lú ilé iṣẹ́ Marlian Records ni ó kéde ìyapa àti yíyan Alákòso tuntun fún iṣẹ́ orin rẹ̀..
wikipedia
yo
Ni ojo karun (5) October 2022, Mohbad fi esun kan naira Marley (oga re nígbàkan) pe oun dunkoko mo oun o si n ran awon kan lati maa na oun kaakiri.leyin iku mohbad ni o han sita wipe saaju ni o ti kowe si ajo olopa ni June 2023, ninu eyi ti o ti fi esun kan Samson Erinfọ̀lami Balogun (Sam Larry) Ore naira Marley, ti o je Olu-gbe-orin okan wipe o fi iya je oun l'ona aito o si tun ba dukia oun je..
wikipedia
yo
Ó tún tẹ̀síwájú nínú ìwé náà wípé Sam Larry kó àwọn ọkùnrin márundógún lẹ́yìn wa pẹ̀lú àwọn ohun ìjà bí ìbọn àti àdá ní ọwọ́ wọn wá sí ibi tí òun ti ń ṣe ìyàwòrán orin tí wọ́n sì wípé wọ́n ṣiṣẹ́ fún ọba ẹlẹ̀gùshi..
wikipedia
yo
Àjọ Ọlọpa sọ wípé Mohbad kó padà yọjú sí àgọ́ wọn lẹ́yìn tí wọ́n fi ìwé pè láti wà fún ìjíròrò lórí ìwé ẹ̀sùn tí ó kọ, àti wípé Sam Larry àti àwọn míràn tí ó fi ẹ̀sùn kan ti kọ́ ìwé ìbánilórúkọjẹ́..
wikipedia
yo
Oba Elegushi se sejade lodi si ìbáṣepọ̀ pelu Samson Erinfọ̀lami Balogun (Sam Larry), o si ranse ibanikedun nipa iku ileriOLUWA OlaDimeji Aroko (Mo-Badmo-bad ni ọmọkunrin kan pelu aya rè Omowunmi, ti wọn bi ni April 2023..
wikipedia
yo
MohBad kú lẹ́yìn tí ó lọ gba ìtọ́jú ní ilé ìwòsàn ní 12 September, 2023 ni ọmọ ọdún mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n (27)..
wikipedia
yo
Àjọ Ọlọpa kéde láti ṣe ìwádí irú ikú tí ó pa olórin náà lẹ́yìn tí wọ́n wú òkú rẹ̀ síta ní 21 September, 2023.Ní ọjọ́ 21 Oòu Kabe, ọdún 2023, níràn Adéàjàláti kọ̀wé nínú ìwé ìròyìn Punch pé Mohbad “jọ àbínibí púpọ̀ àti ní ìbámu pòlu omi Orin gan-an".Nígbà oníwàásù Nàìjíríà àti búlọ́ọ̀gì tí ó dá ni Warri, Isaiah ogédégbé, tí ó àpèjúwe rọ̀ mọ́hBad bí "ọ̀kan nínú àwọn akọrin nlá júlọ ní gbogbo àgbáyé”.Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Àyípadà ojú ọjọ́ ló ti fa oríṣiríṣi ìtànkalẹ̀ ààrùn àti Àìlera Pápá èyí tó farapẹ́ ti omi..
wikipedia
yo
Ipa àyípadà ojú ọjọ́ ló ti wa kãkiri àgbáyé nínú ọ̀gbẹlẹ̀, ìkún omi, ọjọ́ rirò tó lágbára àti omi tó lọ́wọ́rọ..
wikipedia
yo
Èyí ló fa ààrùn omi tó sì tú bo pósí kákiri àágbáyé..
wikipedia
yo
àlékún òtútù àti ìyípadà nínú òjò mú kí ààrùn omi jẹ́ ọ̀kan èyíkéyìí nínú ipa ètò ìlera tó wá látara àyípadà ojú ọjọ́.Ààrùn omiààrùn omi jẹ́ àwọn àìsàn tó wá láti ara kòkó tí àkọlé fojúrí tó wà nínú omi..
wikipedia
yo
Àmì àìsàn náà ni ìgbé gbùrù, ìba, àìlera àti bíbàjẹ́ ẹ̀dọ̀.Àyípadà ojú ọjọ́ ti kó ipa nínú ìtànkálẹ̀ àwọn kòkòrò dífojudi yí,lára àwọn àìsàn náà ni àìsàn àtí Olùmò san tó wa látàrí mímu tí kò da tàbí lílò wọn Èyí ló sí tí fà ikú àìmọye àwọn ọmọòde..
wikipedia
yo
Àìsàn igbẹ́gbùrù ti ṣe okunfa iku awon eniyan Archlli 1.4–1.9 lagbaye..
wikipedia
yo
Gẹgẹbi ajọ ijọba to da lori igbejo ti ayipada oju ọjọ eyi ti Olóyìnbó mosi "Intergovernmental Panel on Climate Change (IPCC)", àlékún ti ba itankale aarun omi gbesin ayipada oju ojo.Ipa ti ayipada oju ojo ko ninu aarun omiiwọn otutu ati ooru iwọn alékún ooru fa àlékún kòkòrò àìfoju ninu ara awon ẹranko ati ninu omi mimu..
wikipedia
yo
Nígbà ooru, omi mímu jẹ́ àlékún èyí ló máa fa ìtànkálẹ̀ àwọn kòkòrò yọ̀yọ̀ tí òun fa ààrùn omi bí ìgbẹ́ gbùrù..
wikipedia
yo
Ní agbègbè tó gbóná pápá èyí tó ní omi kékeré àlékún wà nínú omi tí wọ́n gbà tí wọ́n sì tún lò padà..
wikipedia
yo
Èyí lè fa àlékún ninu omi tí ó ti dọ̀tí.Òjò ati ìkún omi àyípadà ojú ọjọ́ ti fa àlékún bá ọjọ́ rírọ̀ èyí ló fa àìmọye ìkún omi..
wikipedia
yo
ìwádí ṣọpẹ́ ààrùn Iyín gbùrù àti ikùn jẹ́ ọ̀kan lára ipa ọjọ́..
wikipedia
yo
Látara ọjọ́ tó pọ̀ ló fa àlékún bá kòkòrò fojufoju tó sì kó ìparun bá ìmọ́tótó àti omi agbègbè náà..
wikipedia
yo
Ìkún omi kó ipa lórí ètò ìlera, kòkòrò ìgbàanì tó wá láti Igbóṣe àwọn ènìyàn tàbí ẹranko tó wà ní inú ilẹ̀ kó ìparun bá omi ilẹ̀ tó sì máa nkóbá àwọn ènìyàn tó bá mu irú omi náà.Òjò tó bá lágbára máa da omi odò pọ̀ mọ́ omi tó wá láti ṣáláńgá tó sì jẹ́ àkóbá fún omi mímu tó wá láti ilẹ̀.Ìkún omi jẹ́ ọ̀kan lára okùnfà àlékún tó bá ààrùn omi pápá ní orílẹ̀ èdè tó ti dàgbà sókè ní àwọn agbègbè tí àkóbá ti bá omi mímu wọn.Ọ̀gbẹlẹ̀ ọjọ́ ni àwọn agbègbè kan ló ti fa ọ̀gbẹlẹ̀ sí agbègbè tí òjò kò rọ̀..
wikipedia
yo
Èyí ló fa ẹkún bá àwọn ìdọ̀tí inú omi kíwọ́n kúrò, èyí ló mú kí kòkòrò fojudi dojúkọ ìwọ̀n bá omi tó wà ní agbègbè náà..
wikipedia
yo
Ọ̀gbẹlẹ̀ tun maa nje ki àwọn ènìyàn gbẹkẹle omi Ojo àti omi Ẹti ọ̀nà èyí ló máa fa Àkóbá látara kòkòrò àìfojúrí tó máa nfa Aiku omi.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ipa àyípadà ojú ọjọ́ nínú ẹ̀kọ́ ọ̀gbìn ti jásí èrè oko kékeré àti onjẹ ìyè nitori ọ̀gbẹlẹ̀, ooru ìgbì àti ìkún omi èyí ló fa àlékún bá ajẹnirun àti ààrùn ohun ọ̀gbìn.Ipa láti àyípadà àpẹrẹ ojú ọjọ́àyípadà ninú ojú ọjọ́ kó ipa ninú agbègbè fún iṣẹ́ àgbẹ̀..
wikipedia
yo
Ooru máa ńjẹ adikun fún ìkórè ọ̀gbìn ní gbogbo agbègbè bí ilẹ̀ Canada àti apá àríwá ilẹ̀ U.S..
wikipedia
yo
Opolopo oun ogbin lo maa ńbàjẹ́ nitori ooru.Ni odun 2018, ooru nitori ayipada oju ojo fa àdínkù ba ikore ogbin papa julo ile Europe..
wikipedia
yo
Ní oṣù August, ọ̀pọ̀lọpọ̀ òun ọ̀gbìn ló bàjẹ́ èyí ló fà ọ̀wọ́n oúnjẹ ní àgbáyé.Ọ̀gbẹlẹ̀ àti ìkún omi máa jásí àdínkù ìkórè ọ̀gbìn èyí ló ma jásí ìparun ọ̀gbìn àti oúnjẹ..
wikipedia
yo
Ọ̀gbẹlẹ̀ ni àwọn ilú tó dàgbàsókè máa nfà iyán àti àìjẹunrekánú.Fífi omi sí nkan ọ̀gbìn dínkù èyí ló ma fa àdínkù ba ìkórè ọ̀gbìn..
wikipedia
yo
Nitori àìrí òjò, àtirí omi fun nkan ogbin je ìnira nitori pe latari ọ̀gbẹlẹ̀ ọpọlọpọ odo lo maa ngbe eyi lo mu wiwa omi losi ibòmíràn.Nitori afikun aropin iwọn gbígbóná tabi òtútù, ọ̀gbẹlẹ̀ wọ́pọ̀ ni ile Africa, Australia, guusu Europe ati Asia..
wikipedia
yo
Àwọn àgbẹ̀ máa ńkúrò ní agbègbè kan lọ sí ìbò míràn nítorí ọ̀gbẹlẹ̀.Àyípadà Ojú ọjọ́ nínú ajẹnirun, ààrùn ohun ọ̀gbìn àti koríkoàfikún aropin ìwọ̀n gbígbóná tàbí òtútù kó ipá nínú ajẹnirun, ààrùn ọ̀gbìn àti koríko èyí ló fa àdínkùn bá ìkórè ọ̀gbìn.Kòkòrò foju ti kò pa nínú ẹrẹ̀ oko àgbáyé, ìpele yí lè fa àlèkú bá òun ọ̀gbìn àti ìdàgbàsókè àwọn ajẹnirun..
wikipedia
yo
Ìgbà ooru máa fa àlékún bá ìsókè bá kòkòrò inú ọkọ̀..
wikipedia
yo
Àwọn ẹ̀yà kòkòrò yìí ni wọ́n tètè máa ńbímọ nítorí àyípadà ojú ọjọ́.Ìkún Omi tàbí ọjọ́ tó lágbára máa nfa àlékún bá ìdàgbàsókè àwọn ajẹnirun ọ̀gbìn àti ààrùn..
wikipedia
yo
Ọ̀gbẹlẹ̀ ni apá kan maa nfa ìdàgbàsókè oriṣiriṣi ajẹnirun bi kòkòrò Apìkọ̀sẹ̀, ẹ̀fọn funfun àti Èṣù.Àyípadà Ojú ọjọ́ lè jásí ooru èyí ló ma fa ki eṣù bọ àwọn oko nibi ti wọn ti ma ba òun ọ̀gbìn jẹ́..
wikipedia
yo
Èyí ti ṣẹlẹ̀ ní orílẹ̀ ède ila oorun Áfríkà ní ìbẹ̀rẹ̀ ọdún 2020.ìṣirò àwọn ìṣè́ ìrúgbìn àkòní àgbáyéní ọdún 2007, ìwọ̀n àyípadà ojú ọjọ́ ṣe àlékún bá òun ọ̀gbìn látàrí ọjọ́ ṣùgbọ́n kìí orírí agbègbè..
wikipedia
yo
Àkànṣe ètò sọpé èyí lè dínkù ẹbí lagbaye ní ọdún 2080 pẹ̀lú àfiwé ìpele ọdún 2006.
wikipedia
yo
Àwọn ìpèníjà tó pàtàkì wá láti òun ọ̀gbìn tó gbẹ́kẹ̀lé omi tàbí tí wọ́n wà ní agbègbè tí ó gbóná..
wikipedia
yo
Igbimọ iwadi apapọ ti us sise lori ipa ayipada oju ojo lori ikore irugbin ni odun 2011..
wikipedia
yo
Ìṣirò wọn nipé àyípadà nínú ìkórè le dínkún tàbí lékìn..
wikipedia
yo
Iwadi ọdun 2014 Sope ikore irugbin le dinku ni arin keji orundun pẹlu ipa to lagbara ni agbegbe ti Trona ju agbegbe iwọn otutu lọ.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Weekend Getaway jẹ́ fíìmù ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tó jáde ní ọdún 2012..
wikipedia
yo
Desmond Elliot ní olùdarí fíìmù àgbéléwò yìí, àwọn òṣèré tó kópa nínu rẹ̀ ní Genevieve Nnaji, Ramsey Nouah, Monalisa oṣó, Ini Edo, Suth Nwachukwu, Alex Ekubo, Bryan Okwàrà, Beverly Naya àti Uru èké..
wikipedia
yo
Wọ́n yàn án fún àmì-ẹ̀yẹ mọ́kànlá, ó sì padà gba àmì-ẹ̀yẹ mẹ́rin nínu rẹ̀ ní ayẹyẹ Nollywood & African Film Critics Awards (NAFDACA), ti ọdún 2013..
wikipedia
yo
Wọ́n sì tún yàn án fún àmì-ẹ̀yẹ méjì ní 2013 Best of Nollywood Awards pẹ̀lú Alex Ekubo tó padà gba àmì-ẹ̀yẹ fún òṣèrékùnrin tó dára jù lọ..
wikipedia
yo
Fíìmù yìí ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àṣeyọrí nípa ètò owó-ìdìsí, nítorí àwọn gbajúmọ̀ òṣèré tó kópa nínu rẹ̀.Cast Genevieve Genevieve Nnaji Nouah Nouah Monalisa Wọnls Ini Edo Suthchukwu Beverly Naya Alex Ekubo Bryan Okwàrà Uru Uru Ẹ Mogb Nkanga Oyinmo Smọ́ Bobby Ocedo Ìtọ́kasí Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
ìtìjúchukwu Nwachukwu (tí wọ́n bí ní 3 August 1982) jẹ́ òṣèrékùnrin àti olóòtú ètò ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ já..
wikipedia
yo
Ó wá láti kọ̀ọ̀kanjà, Aboh Kingdom, agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Ndokwa East, Ìpínlẹ̀ Delta, ní Nàìjíríà.ibẹrẹṣeìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ àpapọ̀ wá láti ìdílé elénìyàn mẹ́fà..
wikipedia
yo
Ipinle Delta ni o dagba si, ni ughhelli loju opopona ùlọho..
wikipedia
yo
Ile-iwe igbenedion education Center lọ lo lati ọdún 1993 wo 1999..
wikipedia
yo
O gboye eko ninu imo computer Science ni University of Nigeria in Nsukka ati oye Bachelor's degree lati Benson Idahosa University ni Benin City.Àtòjọ Awọn fiimu rẹ The Changer Finding Mercy Bursting Out (Film) Nnda in the Cupboard broken Silence Weekend Getaway deep Inside whose meal ticke Aki and Paww Love is in the Hair Chief karí 10 Days in sun Cityawọn itọkasi..
wikipedia
yo
Bryan Okwàrà tí wọ́n tún mọ̀ sí Ikenná Bryan Okwàrà (tí wọ́n bí ní 9 November 1985) jẹ́ òṣèrékùnrin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tó wá láti ẹ̀yà Ìgbò..
wikipedia
yo
Ó kópa nínú ìdíje kan, tó sì jẹ́ olúborí, tó sì tún gba àkọ́lé Mr..
wikipedia
yo
Nigeria ni ọdún 2007.Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀ If I Am President 2018 the WasHerman 2018 Crazy People 2018 Enàpèjẹ 2016 The Matmaker 2015 Beauty of The Mind 2014 The ÀwaKening 2013 Weekend Getaway 2012Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Uru èké (tí wọ́n bí ní October 11, 1979) jẹ́ òṣèrébìnrin tí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Àṣàgbéjáde fíìmù àgbéléwò..
wikipedia
yo