cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Lọ́wọ́lọ́wọ́, oun ni agbẹnusọ fún igbákejì Ààrẹ ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ìyẹn Prof..
wikipedia
yo
Ṣáájú kí ó tó di agbẹnusọ fún igbákejì Ààrẹ, Àkàndé ń jábọ̀ ìròyìn fún Empòwe Newswire, èyí tó jẹ́ ilé-iṣẹ́ ìròyìn kan tó wà ní Orílẹ̀èdè Amẹ́ríkà, ó tún jẹ́ North America Bureau Chief fún The Guardian ní Ìlú New York, ní America.ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ Ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ ìlú Ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ni wọ́n bí Àkàndé sí..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti Ọmọlẹ́wà, àti Loyola College, ní Ibadan..
wikipedia
yo
Ó parí A-Levels ní ilé-ẹ̀kọ́ gihga ti Oyo State College of Arts and Sciences, ní ilé-Ifẹ̀..
wikipedia
yo
ó kàwé gboyè ní Yunifásítì ti Ìbàdàn ní ọdún 1990, ó sì tún gboyè Masters ní Yunifásítì kan náà ní ọdún 1992.Àwọn iṣẹ́ rẹ̀ ọdún 1989 ni Àkàndé bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ nínú iṣẹ́ ìròyìn kíkọ, ní ọdún 1989, nígbà tí ó darapọ̀ mọ́ ìwé-ìròyìn The Guardian gẹ́gẹ́ bíi ajábó Ìròyìn.Akande jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ News Magazine team niọmọọmọ tí wọ́n dá sílẹ̀ ní ọdún 1993, gẹ́gẹ́ bíi Akọ̀wé àgbà..
wikipedia
yo
Ó sì tún ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Tempo publication nígbà tí ìjọba ológun fagi lé The News fún ìròyìn rẹ̀ lórí ìṣẹ̀lẹ̀ kí òmìnira tó dé.àwọn Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn àtíàwọn oníròyìn ará ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Adébọ̀, tí orúkọ àbísọ rẹ̀ jẹ́ Ọlániyan (tí wọ́n sì bí ní ọdún 1928) jẹ́ ọ̀mọ̀wé àti Nursí ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1984, ó di ọ̀jọ̀gbọ́n àkọ́kọ́ nínu ìmọ̀ Nurnsi ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ìgbésí ayé rẹ̀ a bí Adébọ̀ ní ìlú Abeokuta, ìpínlẹ̀ Ògùn, ní ọjọ́ kẹta oṣù kẹta ọdún 1928..
wikipedia
yo
O bere ipa re ninu ise Nursi ni London, ibẹ̀ lo ti ko nipa ise Nursi ati gbigbebi ni St Mary's Hospital, London laarin ọdun 1957 si 1958..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1959, ó padà sí Nàìjíríà láti di Nursi ní Ìbàdàn..
wikipedia
yo
Ninu ìmọ̀ iṣẹ́ Nursì ní ọdún 1961, ati àmì ẹ̀yẹ Bachelor of Nursing ní ọdún 1962..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ìgbà tí ó ṣiṣẹ́ díẹ̀ gẹ́gẹ́ bí yíd ìmọ̀ràn ní School of Hygiene ti ìlú Ìbàdàn, ó di olùkó ní Yunifásitì ìlú Ìbàdàn..
wikipedia
yo
O dara po mo eka ise Nursi ni osu kewa odun 1967, o si di adari ẹka naa ni odun 1970.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Folashade Adefisáyọ̀ je olukọ ati omowe ọmọ orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
Oun ni Komisona fun ẹka ipinlẹ Eko ti o n ri si eto Eko.eto ẹkọ rẹ o lọ ile iwe Yunifasiti Ilu Ibadan nibi ti o ti gba ami ẹyẹ Bachelor ninu Imọ Zòòlọ̀gy..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn náà, ó tẹ ẹ̀kọ́ rẹ̀ síwájú ní Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Èkó níbi tí ó ti gba àmì ẹ̀yẹ Master degree nínú ìmọ̀ ìdarí owó àti àmì ẹ̀yẹ Master degree nínú ìmọ̀ ẹ̀kọ́ ní Yunifásítì tí Nottingham.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
DiHya, tí wọ́n ń pè ní Alkahina(PA), jẹ́ ọbabìnrin ìlú Berber ti Aures bẹ́ẹ̀ náà ló jẹ́ olórí ẹ̀sìn àti Olórí àwọn ológun tó tako Muslim Conquest of the Maghreb, agbègbè tí wọ́n pè ní Numidia tẹ́lẹ̀ rí tí ó sì máa ń ṣẹ́gun àwọn ọmọ-ogun UMayyad nínú ogun Battle of Meskíàná lẹ́yìn náà ni ó di adarí fún gbogbo Maghreb láìsí olùdíje tó takòó, kí wọ́n tó ṣẹ́gun rẹ̀ ní ogun battle of Taka..
wikipedia
yo
Ninu èdè Arabic ni ipilẹ orúkọ rẹ Al-kaFílístínì ti wa(eyi to tumọ si oluwo aríran)..
wikipedia
yo
Èyí ni orúkọ tí àwọn akẹgbẹ́ rẹ̀ tó jẹ́ Musulumi nítorí ànfàní tó ní láti rí ohun tí yóó ṣẹlẹ̀ ní Ọjọ́-iwájú.Ninu ẹ̀yà Jrawa Znátà ni wọ́n bí í sí ní ìbẹ̀rẹ̀ Sétúrì Keje..
wikipedia
yo
Ọdún márùn-ún ni ó fi darí ìpínlẹ̀ Berber láti orí-òkè Aures Mountains dé ilẹ̀ ọlọ́ràá Gadames (695–700 Ad)..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n àwọn arábó ti Musa Bin nusayr darí padàl pẹ̀lú àwọn ọmọ òògùn tó lágbára láti borí rẹ̀..
wikipedia
yo
Ó ja pẹ̀lú el dd ṣùgbọ́n wọ́n pa nínú ìjà ní ẹgbẹ́ kọ̀nga tó sí ń jẹ́ orúkọ rẹ̀ Birbir Al Kasábàá ní Aures.Oun tí a rí gbo lati Britúrì Orich ní ní pé ọmọ agbègbè jẹ́w ni tàbí pé ẹ̀yà rẹ̀ jẹ́ Judazed Berbers..
wikipedia
yo
GẸ́GẸ́ BÍH ohun tí Al-Lethe sọ, òrìṣà kan ló sí i lọ nínú Damajo rẹ̀..
wikipedia
yo
Mohamed talbi ati Gabriel camps tú òrìṣà yìí sí akọni àwọn kìrìtẹ́nì kan, yálà tí Kiyínjè tàbí tí Wdíà, tàbí ẹni mímọ́ kan tó ń dábọ́bò ọbabìnrin..
wikipedia
yo
M'tọrọ hassine fantar gbàgbọ́ pe akoni duro gege bi orisa Berber, eyi to tumọ si pe ẹlẹṣin Berber ni..
wikipedia
yo
Àmọ́, pé diHya jẹ́ kìrìtẹ́nì àhesọ lásán ni.àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
yẹ́nnenga jẹ́ ọmọ-bìnrin Arosọ, tí a kà sí ìyá tí àwọn ènìyàn Mossi ti Burkina Faso..
wikipedia
yo
Arábìnrin olókìkí jagunjagun tí ó ṣe iyebíye fún bàbá rẹ̀, náà gbewaa tàbí nedega, olùdásílẹ̀ ìjọba dagbọ̀n, ní báyìí ní Ghana lónìí..
wikipedia
yo
Ṣugbọn ọmọ-bìnrin ọba nífẹ̀ẹ́ sí àyànmọ́ mìíràn ó pinnu láti lọ kúrò ní ìjọba náà..
wikipedia
yo
Bí ó ti ń sáré pẹ̀lú ẹṣin rẹ̀, ó pàdé ọ̀dẹ̀dẹ̀ odò kan, riale tí ó bí ọmọ kan pẹ̀lú rẹ̀ tí a ń pè ní Ouedraogo..
wikipedia
yo
Ouedraogo jẹ́ orúkọ ìkẹhìn olókìkí ní Burkina Faso àti túmọ̀ sí "Ẹ̀sìn akọ" ní Ọlà fún ẹ̀sìn tí ó darí Ọmọ-bìnrin Ọba sí rialé..
wikipedia
yo
yẹ́nnenga tàbí ọmọ rẹ̀ Ouedraogo ni a kà ní olùdásílẹ̀ ti àwọn ìjọba mọ̀ssí..
wikipedia
yo
Orísirísi ìyàtọ̀ ló wá wà nípa àwọn ọ̀nà àbáyọ tí ọmọ-ọbabìnrin.àwọn ìtọ́ka sí..
wikipedia
yo
Jorinia Adenike Adeniji (tí a bí ní ọjọ́ karùndínlọ́gbọ̀n osù keje ọdún 1971) jẹ́ ọ̀mọ̀wé àti ọ̀jọ̀gbọ́n ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O jẹ igbakeji ojogbon ninu imo didari oko owo ni Yunifasiti Covenant, Ipinle Ogun, Naijiria.ipilẹ ati Eko re won bi Adeniji ni ojo karundinlogbon osu Keta-an odun 1971, ni ilu Ota, ti Ipinle Ogun State..
wikipedia
yo
rẹ́ ninu imo idari oko Owo ni odun 1995 ni Yunifasiti Olabisi OnaBanjo..
wikipedia
yo
O gba ami-eye post graduate diploma in Financial Management (pgdFM) ní ọdún 1997 ní Yunifásítì Obáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ ní lo tún ti gba àmì-ẹ̀yẹ M.B.A..
wikipedia
yo
Felicia Adébọ́lá Adeyọyin (tí a bí ní Ọjọ́ Kẹfà Oṣù kọkànlá Ọdún 1938 tí ó sì fi ayé sílẹ̀ ní ọjọ́ Kínníi Oṣù Ka-un ọdún 2021) jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ní Yunifásítì ìlú Èkó àti ọmọ Ọba ní ilé ìdi ní Ṣaikun, Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́..
wikipedia
yo
Oun ni o ko Nigerian National Plellenta.ipilẹ rẹ a bi Felicia àwùjọọlá ni ojo kẹfa Oṣu kọkanla ọdun 1938 ni Ògbómọ̀sọ́, ìpínlẹ̀ Oyo..
wikipedia
yo
Ó lo ìdí-abá, ilé-ìwé Baptist kan ní Abeokuta ní àárín ọdún 1953 sí 1957..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1965, ó fẹ́ Solomon Adedeji Adeyọyin, ẹni tí ó kàwé ní ilé ìwé ìdí-aba's fun àwọn ọkùnrin.Ẹ̀kọ́ rẹ̀ Felicia gba àmì-ẹ̀yẹ Bachelor degree nínú ìmọ̀ Jiografi ní Brkbeck, Yunifásítì London ní ọdún 1968 àti àmì-ẹ̀yẹ diploma of Education ní Yunifásítì kan náà ní ọdún 1976, kí ó tó gba àmì-ẹ̀yẹ M.A..
wikipedia
yo
Ninu imọ̀ Social Studies ni Columbia University ti Ilu New York ni odun 1977, ki o to gba ami-eye PhD rẹ ni ọdun 1981 ni Yunifasiti Ilu Eko.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Cordelia Ainehi agbebaku (tí a bí ní Oṣù Kínní ọdún 1961) jẹ́ ọ̀mọ̀wé àti adarí Yunifásítì Ambrose Alli tẹ́lẹ̀rí.Ìtàn ayé rẹ̀ wọ́n bí Akúkú ní ìlú Ekpoma ní oṣù kinni ọdún 1961..
wikipedia
yo
Ó kọ́ nípa ìmọ̀ òfin ní Yunifásítì Bendel tí a mọ̀ sí Yunifásítì Ambrose Alli lọ́wọ́ lọ́wọ́..
wikipedia
yo
Abaku di adari Yunifasiti Ambrose Alli (AU) ni odun 2014 nigba ti Gomina Adams oshiomhole yan sípò naa..
wikipedia
yo
Abaku fi sile ni ojo kerindinlogun osu keji odun 2017, ni ile iwosan Yunifasiti Benin, o si fi oko re - ojogbon Phillip Abaku ati awon omo re sáyé.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Anuke je orisa atijọ ti o je okan láàárín awon orisa orile ede Egypt ti apa ile nile ati ni owo isale gbogboogbo Nubia, eyi ti o tun je pe awon ara eleAmalekitine naa maa n sin.asp#iru ara ile Egypt tabi awon elédè Egypt a maa pe ni AnuKE, eyi ti won fàyọ lati anaka, tabian anQet..
wikipedia
yo
Orúkọ tí wọ́n fún yìí ń túnmọ̀ sí olùgbnkan tàbí ẹnití ó ń di nǹkan mú..
wikipedia
yo
Ní ilẹ̀ Greece, èyí di Anoúkis, (), ìgbà mìíràn en máa ń kò ní Anukis..
wikipedia
yo
in the interpresee Graeca, she was considered equIVIValent to hestia or vesta.Àwọn àpèjúwe wọn máa ń ṣàpèjúwe AnuKE gẹ́gẹ́ bí obìnrin tí ó ní agbekori bí ti gèlè tàbí irun tí wọ́n fi ìyẹ́ ẹyẹ sàdára sí irun náà..
wikipedia
yo
Wọ́n sábà máa ń ṣàpèjúwe rẹ̀ pé ó di ọ̀pá àṣẹ kan mú tí wọ́n fi lákh sórí ọ̀pá náà, ẹran mímọ́ rẹ̀ sì jẹ́ àgbọ̀rín..
wikipedia
yo
She was also shown ṣuckling the Pharaoh through the new Kingdom and became a goddess of lust in later years..
wikipedia
yo
In later Periods, she was associated with the sáwọn, especially the shell, which resepunoni the vagina.Ìtàn ati àwọn ipáo jẹ ọmọ bíbí òrìṣà rà, ṣugbọn ó tàn mí ṣat ní àwọn ayé ibòmíràn..
wikipedia
yo
Fún àpẹẹrẹ, àwọn oriṣa mejeeji yìí ni wọ́n ń pè ní "Ojú ra" [Ẹyẹ of Ra], pẹlu àwọn bíi Bstet, HnnHor, ati Sekhmet..
wikipedia
yo
also, they were both related in some way to the uraeus.Iìsìn tabi ijosinanu jẹ ọkan lara awon orisa meta, orisa Khnum ati orisa ṣa€ ti won tun pe ni Milọrun..
wikipedia
yo
O silẹ jẹ pe AnuKE ni aburo obinrin si ṣaJIT tabi Milai..
wikipedia
yo
Or she may have been a junior consort to kh instead.Wọn ko Temple ilé ìjỌsìn kan fún AnuKE tí ó wà ní ilẹ̀ Sehehe ní ilẹ̀ SeheArá..
wikipedia
yo
àwọn àlùlù kan fihan pé ojúbọ kan tàbí pẹpẹ kan ni wọ́n yà sí mímọ̀ fún-ún ní ojúlé yìí láti ọwọ́ Ọlọ́fin 13th Fáráò Desote III III..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn náà, nígbà ìṣàkóso kejìdínlógún, Amenhotep II ya ilé ìsìn kan sí mímọ́ fún òrìṣà.Ní àkókò ìjọba tuntun, àṣà Ajant ní ilé Elegbàdúràtine ni kìí wọn lo odò fún ìṣẹ̀ṣe òrìṣà náà ní oṣù àkọ́kọ́ ti Shemu..
wikipedia
yo
Àwọn àkọọ́lẹ̀ dárúkọ àwọn ìlànà tí wọ́n n gbà ṣe àjọ̀dún ti khó àti AnuKE ni àsikò yìí.Lọ́pọ̀ ìgbà, nígbà tí odò Naili bá ti bẹ̀rẹ̀ sí ní kún fún omi olóọ̀ọ́dún, àjọyọ̀ àjọ̀dún AnuKE bẹ̀rẹ̀ nìyẹn..
wikipedia
yo
Àwọn èè a maa so àwọn ohun bíi ẹyọ owó, wúrà tàbí góòlù, àwọn ohun oso àti àwọn ẹbu ìyìlù sínú odò náà, lati ṣe ìgé fún Orì náà fún omi tó ń fúnni ní iye àti àwọn anfaani tó ń pa pa wa látinú ọ̀rọ̀ àti ìbímọ tí ó ń ń ṣàmọ̀. ohun òlo ti o wáyé ní àwọn agbègbè kan ní àwọn kí ilé Egypt, èyí tí àwọn ọmọ pé ẹjò kan tí a kà sí mí jẹ́ èèwo fún wọn, padà wà ní gbajúmọ̀ ní àkókò yìí, èyí ti wọ́n padà ti wọ́n padà pé irú ẹnu tí ọdún náà ti odo ibi ẹ̀ibi pé ohun ní kìí ni kìí pa wọ́n fún ìpé gẹ́gẹ́ gẹ́gẹ́ bí àwọn ohun ìlẹ̀. fún ìguyàn wa ìdáru- ọdún citation}} fún ikàn fún ìka ẹ̀rus náà tí River-s Hatogi- River of River Playrs..
wikipedia
yo
1665) jẹ́ ọmọ obìnrin tí ọba kan tí wọn kò mọ orúkọ rẹ̀ ní ìlú Manikóńgò..
wikipedia
yo
gẹ́gẹ́ bí àṣà, ó jẹ́ ìyá Ganga Zìfà àti ìyá tí ó bí ìyá Zumbi..Ní ọdún 1665, Aqual] jẹ́ olórí ọmọ ogun ẹgbẹẹgbẹ̀run ọkùnrin àti obìnrin fún kóńgò lọsí ogun MB, níbití ó ti ṣẹ́gun àwọn ọ̀tá rẹ̀..
wikipedia
yo
Nígbà èyí, wọ́n gbé lọ sí Port ti Recife], ilé-ìtajà àti ilé iṣẹ́ ọlọ ṣúgà..
wikipedia
yo
Wọ́n rà gẹ́gẹ́ bí ẹrú, lẹ́yìn náà wọ́n tún ta sí ọlọ kan ní Porto calvo, ní bẹ́ẹ̀ ni ó ti lóyún.Lẹ́yìn tí ó bọ́ ní oko ẹrú yìí, ni ó de Palmares ní quìlòmbọ̀..
wikipedia
yo
Ó di olórí àti adarí ṣubúpúial ní quìlò-Àkókó, èyí tí ó wà ní apá àríwá oòrùn agbègbè kan ní Palmares..
wikipedia
yo
Ó bí ọmọ ọkunrin meji, tí wọn ń jẹ gangan Zbọ́gbọ́n ati gan sọ́nà, èyí tí àwọn náà pada di adarí ati olórí ìlú Palmares..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn gbogbo èyí, a kò mọ ohun tí ó padà gbẹ̀yìn ìgbésí ayé àti àyànmọ́ rẹ̀, òkú ikú àràmàdà ní ọdún 1675.Àwọn ìtọ́kasí African Women in Wardate of birth unknown17th-century deathsleselese Royalty17th century in BrazilBrazilian slavesafro-Brazilian people17th-century women rumasrekaWomen in 17th-century warfare
wikipedia
yo
HIwọt Ayalew Yimer ni a bini ọjọ kefa, oṣu March, ọdun 1990 jẹ akosemose elere sísá ti ona jinjin to da lori steeple ti metres ẹgbẹrun meta ti orile ede Ethiopia..
wikipedia
yo
Tigist asṢefa tesṢema ni a bini ọjọ́ keji dinlogbon, oṣu March, odun 1994 je elere sísá ona jínjìn..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí arábìnrin náà kópa nínú Marathon tó wáyé ní oṣù kẹrin, ọdún 2022 ló gbìyànjú sí lórí ìṣẹ́jú méjì dínlógún..
wikipedia
yo
Tigist kópa nínú Marathon ti Berlin níbi tó ti gbé ipò karùn.Ní ọdún 2013, asṣé gba àmì ẹ̀yẹ ti ọ̀la ní Ìdíje Junior ti ilé afiricaàsà..
wikipedia
yo
Sofia asṢefa ni a bini ọjọ́ kẹrinla, oṣu November, ọdun 1987 si ilu Tenta, South Wolo je elere sísá ti ona jinjin to dálórí steeple ti metres ẹgbẹrun mẹta..
wikipedia
yo
Sofia gba ami idẹ ọ̀la ti Silver ní Summer Olympics ti ọdún 2012.ÀṣeyọríSofia kópa nínú ìdíje ilé afirica níbi tó ti parí pẹ̀lú ipò kẹrin ní ọdún 2008..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2019, Sofia parí pẹ̀lú ipò kẹtàlá nínú ìdíje àgbáyé.Ní ọdún 2012, Sofia gba àmì ẹ̀yẹ ọlá ti Silver nínú Summer Olympic tí steeple ti ẹgbẹ̀rún mẹ́ta Metretre.Ní ọdún 2013, Sofia gba àmì ẹ̀yẹ tí ọlá ti idẹ nínu ìdíje àgbáyé tó ààyè ní Moscow.Ní ọdún 2015, Sofia gba àmì ẹ̀yẹ ti ọ̀la ti Gold ní èrè ilé àfizũra tó wáyé ní Brazzaville.
wikipedia
yo
Eskerem AsṢefa lẹ́gẹ́sse wọndimagGN ni a bini ọjọ ogun, oṣu September, ọdun 1985 si ilú Robe, Arsi je elere sísá ti ona jinjin..
wikipedia
yo
Meskerem ṣoju fun orile ede Ethiopia ninu Olympics ti odun 2008 ati 2012.Aṣeyọri M kopa ninu idije Agbaye lori ere Eko lẹẹmeji..
wikipedia
yo
Lucy Ameh (tí a bí ní ọjọ́ kejìlá Oṣù Kẹfà Ọdún 1980) jẹ́ òṣèré àti oníṣòwò ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó gbajúmọ̀ lẹ́yìn ìgbà tí ó ṣeré nínu eré Bra106 on a bald head ní ọdún 2010.Àyè àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ a bí Lucy ní Kàdúná ní ọjọ́ kejìlá Oṣù Kẹfà Ọdún 1980..
wikipedia
yo
Ó bẹ̀rẹ̀ sí ń ṣe eré ìtàgé nínú ilé ìjọsìn rẹ̀ nígbà tí ó sì jẹ́ ọmọdé..
wikipedia
yo
Ó kàwé gboyè ní NTA TV College, ó sì gba àmì-ẹ̀yẹ B.Sc nínú ìmọ̀ Mass Communication ní Yunifásítì Vwá Bello, Zaria kí ó tó tẹ̀síwájú láti gba àmì-ẹ̀yẹ diploma in Law ní Yunifásítì ìlú Jos.eré ṣíṣe Lucy bẹ̀rẹ̀ sí n ṣe eré ìtàgé láti ìgbà èwe rẹ̀, ó kópa nínu ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré kí ó tó kópa nínu eré 'Queen of ZaSiriaau', èyí tó mú kí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn mọ.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Al-kahina (), tí a mọ̀ sí DiHya, jẹ́ Berber Ọbabìnrin ti Aures àti adarí ẹ̀sìn àti àwọn ológun tí ó máa ń lé wájú àwọn aláàbò ọmọ ìlú sí Muslim Conquest of the Maghreb, ẹṣin tí wọ́n padà mọ́ sì Numidia tí ó hàn pé wọ́n ń ṣẹ́gun àwọn ọmọ ogun UMayyad nínú ogun ti Meskiana lẹ́yìn tí ó ti di adarí tí kò díje ti gbogbo ilẹ̀ Maghreb, kí wọ́n tó fi ẹ̀tànjẹ ṣẹ́gun rẹ̀ ní Ogun TaBarka náà..
wikipedia
yo
Wọ́n mẹ́nuba ipò rẹ̀ ninu èdè Lárúbáwá tí ìpìlẹ̀ rẹ̀ jẹ́ Al-kaees (the priesess Sooth )..
wikipedia
yo
Èyí ni orúkọ inagijẹ tí àwọn Musulumi olùbál rẹ soo nítorí ẹ̀bùn riri ìṣẹ̀lẹ̀ ọjọ́-iwájú.Wọ́n bíi sínú Jrawa Znátà àwọn ẹ̀yà Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ 7th Century..
wikipedia
yo
Fún ọdún gbáko ni ó fi darí ìpínlẹ̀ Berber tí ó ní iyánnda láti Aures Mountains náà lọ sí ilẹ̀ olómi nínú aginjù Gadames (ní 695–700 Ad)..
wikipedia
yo
Àmọ́ àwọn Arab, ṣàpọ́nlé nípa Musa Bin nusayr, pípadà pẹlu àwọn ọmọ ogun tí wọ́n sanan tí wọ́n sì ṣẹgun rẹ̀..
wikipedia
yo
Ó ja ogun tí el Djem orí-Afara ìdágaǹ ìlẹ̀ RÓÒMÙ mọ́ tí wọ́n paá lẹ́yìn ẹ-O-lá nínú ikodì kan tí ó sì sí ń jẹ́ orúkọ rẹ̀, Bir Al kahina in Aures.Awon ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
O ni oko iresi Kereksuk ni Ipinle Nassarawa ti o jẹ ile-iṣẹ irẹsi iṣowo keji ti o tobi julọ ni orilẹ-ede Naijiria nipasẹ titobi ilẹ̀..
wikipedia
yo
Oko rẹ̀, èyítí ó wà ní ìpínlẹ̀ Nasarawa ní àríwá Nàìjíríà, wà lọ́wọ́lọ́wọ́ ní àwọn saare 45,000 àti pé ó gba bíi òṣìṣẹ́ 600 tí wọ́n jẹ́ ọmọ abínibí ìlú Nasarawa.Èkó Ó lọ sí ilé-ìwé girama King's College, ní ìlú Èkó..
wikipedia
yo
Ó kọ́ ẹ̀kọ́ ètò-ọrọ̀ ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti Aberdeen, ní oŕlẹ̀-èdè Scotland àti pé ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè Masters ní Ìṣòwò láti ilé-ẹ̀kọ́ kan náà..
wikipedia
yo
O te siwaju si School of Oriental and African Studies (SOAS), ni ibi ti o ti gba oye Eko Masters nipa Iṣuna ati idagbasoke ijinle.Iṣẹ-sise o sise gege bii Ayanyánna ni European Economics and Financial Center ni Ilu London ni odun 2007..
wikipedia
yo
Ó tẹ̀síwájú láti jẹ́ aṣoo Afirika ní ìwé ìròhìn Euromoney ní ọdún 2008..
wikipedia
yo
Ó tẹ̀síwájú láti ṣiṣẹ́ ní First City Monument Bank ní ọdún 2008 níbi tí ó ti sọ pé àwọn ìdáó rẹ̀ fún ẹ̀ka iṣẹ́-ọ̀gbìn dáwá sì dàgbà nítorí ilé-ìfowópamọ́ kò ní gba àwọn ètò ìmúlò àti kí ó wọlé sí ilé-iṣẹ́ ọ̀gbìn..
wikipedia
yo
Ó kúrò ní ọdún 2010 láti bẹ̀rẹ̀ oko ìsísí hekitari 45,000 ti Kereksuk ní ọdún 2012.àwọn Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn àAlààyèàwọn oníròyìn ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Anne Bonny(8 Oṣù Kẹta Ọdún 1697 - sọnù ní oṣù kẹrin ọdún 1721), ìgbà kan Anne Sanyy, jẹ́ ajalèlókun Irish tí ń ṣiṣẹ́ ní Caribbean, àti ọ̀kan nínú àwọn ajalèlókun obìnrin Díẹ̀ nínú ìtàn-Àkọọ́lẹ̀ tí ó gbàgbà..
wikipedia
yo
Ohun kékeré tí a mọ̀ nípa ìgbésí ayé rẹ̀ wà ní pàtàkì láti inú ìwé Captain Charles Johnson's 1724 A General History of the Pyrates.Igbe aiyé ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ọjọ́ ìbí Bonny ni a rò pé ó wà ní àyíká 1700..
wikipedia
yo
Wọ́n ní wọ́n bí ní orí àgbà Kinsaleshe , ní ìlú County Cork, Ireland..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọmọbìnrin ìránṣẹ́bìnrin Maria Brennan àti agbanisíṣẹ́ Brennan, agbẹjọ́rò William CorMac..
wikipedia
yo
A bí Mary Brennan nítorí atẹle aisan ti iyawo CorMac o gbe lọ si ile iya-ọkọ rẹ ti o wa ni awon mámáì die si ọna..
wikipedia
yo
Lakoko ti iyawo William CorMac n ṣaisan ati ni ile miiran, William duro lati wọ ile ẹbi nibiti o ti ni ibalopọ pẹlu ọkan ninu awọn iranṣẹbinrin, Mary Brennan, eniti o bi Anne Bonny lẹhinna..
wikipedia
yo
Anne Bonny ni a ríi bí ọ̀kan nínú àwọn ọ̀ràn ẹ̀tọ́ lati William CorMac ..
wikipedia
yo