cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Awo ti o fi lole ni 2009 ti o je proṣíṣàṣàrò single re ti o pe ni "If You Want Me"
wikipedia
yo
O kuro ni Knighkéèyàn ni Oṣu Keji ọdun 2012, leytin igba naa ni o da ile ise orin rẹ sile ti o pe ni chedDah Music.ibẹrẹ Ayemo chedDah jẹ ọmọ ti abi ni ojo kerindinlogun osu kẹwàá ni ọdun 1990, ni Ipinle Eko..
wikipedia
yo
O jẹ ọmọ kerin ninu ọmọ márùnún ti awon obi rẹ bi, ti a si le to pinpin re losi Ipinle Osun, eyi ti o je ilu awon obi re.eto ẹ̀kọ̀ọ́ pari eko alako bere re ni University of Lagos Staff School ni , ilu , o si lo si Lady of Apoles, nibi ti o ti pari eto eko girama re..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní iṣẹ́ Creative art láti Fásitì ti ìlú Èkó, .Momọ ched nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún méjì ni ó bẹ̀rẹ̀ ibojì fi Creative side ẹ hàn..
wikipedia
yo
Ní ìbẹ̀rẹ̀, ó ní fẹ́ sì kí a ṣeré orítage, ṣùgbọ́n nígbẹ̀yìn ó bọ́ sí orí orin kíkọ..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí ó kúrò ní Knighníbo ni ó dá ilé iṣẹ́ orin ti rẹ̀ sílẹ̀, tí ó sì pè ní Moched music..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí ó dá ilé iṣẹ́ náà sílẹ̀ ni ó bẹ̀rẹ̀ síní ṣiṣẹ́ lórí àwo orin ẹlẹ́kejì tí ó sì yẹ kí ó gbé jáde ní ọdún 2016..
wikipedia
yo
Yato si ki a ko roin, mo chedDah ni imọ lori bi ati ṣe n ran aṣọ, ti a Moi si.Discography Studio Albums Franchise celebrity (2010) selected Singles "Survive"my time time" “Nasians (featuring Phyno) “Torí Ọlọrun” “Bad for You You” (featuring May d)àwọn Ami Ẹyẹ​this list is ince; You can help by adding missing items..
wikipedia
yo
(February 2016igbe ayé ni Oṣu Karun, ọdun 2018, o ṣe igbeyawo pẹlu ololufẹ rẹ ti o ti pe, Ọmọọba bukunyi Olateru-Olagbegi ni aye kan ni Ipinle Eko ni orile ede Naijiria ..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bi aya Ọmọọba, o ní ẹ̀tọ́ lati lọ àti láti fi olórí' sí iwájú orúkọ rẹ nígbà tí wọ́n bá fẹ́ pe.Àwọn ìtọ́kasíExternal abojọ Modepoda Biography on MTV Base..
wikipedia
yo
Ọmọ-Love Branch (ti wọ́n bí lọ́jọ́ Kẹwàá, oṣù Kìíní ọdún 1974) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá bìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí o máa ń gbá bọ́ọ̀lù ní àyè abo-ilẹ̀ fún ọkọ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin Nigeria..
wikipedia
yo
Ó wà lára ìwa àkọ́kọ́ àwọn obìnrin tí wọ́n sojú Nàìjíríà nínú ìdíje 1991 FIFA Women's World Cup àti 1995 FIFA Women's World Cup.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Wàyí ọláRonke Abiola-costelo (tí wọ́n bí ní ọjọ́ ọ̀kan lé nípọn Oṣù Keje Ọdún 1974) ní ìlú Èkó..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ajàfẹ́tọ̀ọ́ ètò ọmọ Nàìjíríà, àwọn ètò aráàlú, ajàfẹ́tọ̀ọ́ ìjọba ara wa, àti olùdásílẹ̀ Kudirat Initiative for Democracy (kind| èyí tí ó ń wá láti fún àwùjọ aráàlú lágbára àti ìgbélárugẹ ìjọba tiwa-n-tiwa ní ilẹ̀ Nàìjíríà.ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ àti ètò ẹ̀kọ́Abiola-costello ni ọmọ kẹjọ tí Ààrẹ tí wọ́n yàn ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí kò jẹ́, olóyè Moshood Abiola àti olóògbé Kudirat Abiola..
wikipedia
yo
Bàbá rẹ̀, Moshood Abiola, tí wọ́n fi sẹ́wọ̀n l'Owo Aẹbọ gen Sani Abacha fún ìwà ọ̀daràn lẹ́yìn tí ó ti kéde ara rẹ̀ ní àárẹ̀..
wikipedia
yo
Agba Abiola ku nigba ti o wa ni àtìmọ́lé ni odun 1998.[1] Lkoko ti won pa iya re ni akoko ifihan kan fun itusilẹ ọkọ rẹ ni odun 1996.[2] Ni osu kefa odun 2018, Aare Muhammadu Buhari fun un ni olori alakóso fun baba rẹ to ku, Oloye Moshood Abiola, fun eni ti o ye ko jawe olubori ninu idibo Aare ni ojo kejila osu kefa odun 1993..
wikipedia
yo
Abiola-collolo lo ile-iwe giga rẹ ni Queens College, Yaba, Ilu Eko..
wikipedia
yo
O kawe gboye ni ile-ẹkọ giga Phillips Academy, AnDover, ni ọdun 1992 ati Harvard College ní ọdun 1996 nibiti o ti gba oye kan ni eto-ọrọ idagbasoke (Development Economics) ati lẹhin naa gba M.Sc..
wikipedia
yo
Ni International Development lati tsinga University, Beijing.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Oloye Abiola Dosunmu (ti a mo tele si Dosunmu-ìrẹ̀wẹ̀sì-Fernández, a bi ní July 29 1947), jẹ́ oníṣòwò ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ,ó jẹ́ aláfẹ́,àti ó níṣẹ́ ìbílẹ̀ ..
wikipedia
yo
Jessica Oyelowo (née Watson; ti a bi ni 1978) je osere ati ọ̀kọrin ti Bribẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ Bribẹ̀rẹ̀ Aye orúkọ tí wọ́n sọ ní Jessica Watson ní àpswich ó sì dàgbà sí suffolk, ní England..
wikipedia
yo
O losi ile iwe alakọbẹrẹ ti Woodbridge School nigba ti o wa ni Kékeré..
wikipedia
yo
Ó sì jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ National Youth Music Theatre .Iṣẹ́ ní ọdún 2006, òun ló ṣe Detective Sergeant Alex Jones ní Mayo ó sì tún wà nínú eré tí wọ́n pè ní Murphy's Law tí James Nesbitt ná wà níbẹ̀, in 2007..
wikipedia
yo
Equiano (ti oko Mr Equiano naa re si je Husband Olauh Equiano ninu ere Grace UNshackled - the Olalauh Equiano story, èyí tí ó jẹ́ eré ìtàgé tí ó maa ń wáyé lórí tí wọ́n yalo láti Equiano's 1789 Autobiography tí a mọ̀ sí The Interesting Narrative of the Life of Olauh Equiano..
wikipedia
yo
Ti akoko iru rẹ si waye lori BBC 7 ni osu kerin odun 2007.Igbe aye oyelowo n gbe ni Tarzana ni San Fernando Valley ni Southern California pelu ọkọ rẹ ti oun naa je osere ti oruko re si n je David Oyelowo..
wikipedia
yo
Àwọn mẹ́ọ̀fọ̀jì pàdé nígbà tí wọ́n lọ sí London Academy of Music and Dramatic Art..
wikipedia
yo
tí wọ́n n gbé ní Brighton, England.Àwọn mẹ́ẹ́jì sì jẹ́ kiteẹni.oyelọ́wọ́ àti ọkọ rẹ̀ jẹ́ nãbọ̀rìṣàsed us citizens ní 20 July 2016.Gẹ́gẹ́ bí ó ti jẹ́ aya ọmọ Yorùbá yí tí ó tún jẹ́ Ọmọọba , ọyẹ́lọ́wọ́ ní ẹ̀tọ́ sí kí a pẹ́ ní olórí..
wikipedia
yo
Àmọ́ kìí sábà lọ.Filhare work Cyrano de Bergerac (as Roruška) at the Royal Exchange, Manchester, 2006 Ana in Love (play) at Hackney Empire for inside Intelligence 2007 as you like it (Rosalind) for inside Intelligence 1997, her Professional Súnbutáwọn Ìtọ́kasí gbáà
wikipedia
yo
Tanimọwọ́ OgunLesi (1908-2002) je Ajafèéto awon obinrin ile Naijiria o tun je adari women's improvement League..
wikipedia
yo
O je okan lara awon adari to n ja a fun eto awon obinrin ati okan lara awon oludasile National Council of Women Societies, ti n se aṣáájú ileele Ajafèéto awon obinrin ti Naijiria.igbesi aye re tanilo OgunLesi lo ilẹ̀ Kugbo girls school séwudán..
wikipedia
yo
Ó tún kàwé ní ilẹ̀ilẹ̀ United Missionary (um ​ fún ìkàwágboyè iké gẹ́gẹ́ bí i olùkọ́..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ẹni àkọ́kọ́ láti ṣe ìdásílẹ̀ ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ oníléẹgbẹ́ ní ìlú Ìbàdàn (Children Home School)..
wikipedia
yo
O jẹ Aare akọkọ ti National Council of Women Societies ni ọdun1959..
wikipedia
yo
O sise ribiribi lori eto awon obinrin lati ma dibo ati lati ni anfaani si awon ohun-elo Eko, sugbon gege bi i opo awon adari obinrin igba aye rẹ, ko ni ejo to tako si awon okunrin gege olori awon idile orilẹede ile Naijiria.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Kemi Omolọ́lù-Olúnlo (Oluìtumọ̀ Omolọ́lù-idUSLOLORA, tí a bí ní ọjọ́ kẹfà, oṣu kẹjọ,1964) jẹ́ akọ̀ròyìn, ajàfẹ́tọ́, àti gbájúmọ́ ẹran lórí ikanni ayé Nàìjíríà.. Ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ gbajúmọ̀ ní orí ìkànnì ayélujára ní Nàìjíríà, pàápàá jùlọ, fún ṣíṣe àríyànjiyàn lórí àwọn ọ̀rọ̀ tí ó múni lọ́kàn, bí ìfẹ́ònu hàn ti End SARS ní ọdún 2020 àti ikú akẹ́kọ̀ọ́ ilé ẹ̀kọ́ àdáni kan ní ẹ̀kọ́..
wikipedia
yo
Ọmọlọ́lù-lophile ti dojúkọ afisunsun oríṣìí nipa ayé àti iṣẹ́ rẹ; ti púpọ̀ rẹ o si jẹ òtítọ́.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Faith Abiola Oyedépò (born Fbuary 5, 1958) is a Nigerian Preacher..
wikipedia
yo
She is the wife of David nìyíníyì Oyedépò, who is a Christian author, businessman, esperantect, the founder and presiding bishop of living faith church worldwide and also the chancellor of covenant university and landMark University Ẹ̀bictively.faith Abiola Oyedépò is the co founder of faith Academy SecoÌṣọ́ school.she is also a Christian author.she was blessed with four children.David,Isaac,love and Joyceàwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Articles with Hcardsolóyè Alimotu pẹlẹwúrà, (1865-1951) jẹ́ oníṣòwò Nàìjíríà kan tó jẹ́ adarí ẹgbẹ́ àwọn obìnrin ti Ọjà Ẹ̀kọ́, ẹgbẹ́ àgbà obìnrin tí ó jẹ́ oníṣòwò ní Èkó..
wikipedia
yo
O tun jẹ ẹlẹgbẹ oṣelu pataki ti Herbert Macaulay .igbesi aye ibẹrẹ ilu Eko ni wọn ti bi pẹlẹni si idile nla kan..
wikipedia
yo
Ìyà rẹ jẹ onisowo ẹja ati pẹ̀lẹ̀nu tun yan isowo ẹja gegebi ise..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1900, ó ti di aṣáájú àwọn obìnrin àti onísíà ọjà pàtàkì àti ní ọdún 1910, Ọba Eshugbayi Àko fún ní oyè Olori ..
wikipedia
yo
Ni àwọn ọdún 1920, ó jẹ́ aṣáájú ọjà ẹran eréko pẹ̀lú àtìlẹ́yìn Herbert Macaulay, ó dìde lati di olórí ẹgbẹ́ tuntun ti àwọn obìnrin ti ọjà Èkó..
wikipedia
yo
O je omo eya Awori ti YORÙàwọn itọkasi awon ojoalaisi ni 1951..
wikipedia
yo
Charlotte Olajumoke Obasa (ti oruko ibi re n je —ze; ojo keje osu kìíní, odun 1874 si ojo eta le logun osu kẹwàá odun 1953) je eni ara omo orile-ede Naijiria ati oninuure.O je ọmọbinrin onisowo R.B — — iyawo onisegun orisadi Obasa.Aye reSaro Obasa kan ni won bi gege bi i okan lara awon omo Richard Beale Blaize Ship ati ọlọ́jà oloselu, ati iyawo re Emily Cole Cole can
wikipedia
yo
O lo awon odun igbekale re ni ilu Eko, nibiti baba rẹ ti se atẹjade awon iwe iroyin ti orile-ede The Lagos Times ati Gold Coast Colony Advertiser ati the Lagos Weekly Times..
wikipedia
yo
ó ka ẹ̀kọ́ dáradára, àkọ́kọ́ ní ilé-ìwé ti àwọn ọmọbìnrin Anglican lónìí ni ìlú Èkó, lẹhin náà ni ilé-ẹ̀kọ́ kan ni England.Ni ọdún 1902, ó ṣe igbéyàwó si ọmọ Ọba Saro, Prince Òrìṣàdipé Obasa..
wikipedia
yo
Baba rẹ̀ fún tọkọtaya ní ilẹ̀ titun kan gẹ́gẹ́ bí ẹ̀bùn igbeyawo; nígbẹ̀yìn náà ni wọ́n wá ń pè é ní ilé babafunmi..
wikipedia
yo
Obasa àti ọkọ rẹ̀ tẹ̀síwájú láti bí ọmọ márùn ún papọ̀.Ẹ̀gbọ́n sì lẹ́hìn, Lady Ademola, Obasa jẹ́ òǹtajà àti onínúure tí ó ṣe àgbéga ètò àwọn obìnrin àti ẹ̀kọ́..
wikipedia
yo
Ni ọdun 1907, ile-iwe àwọn ọmọbinrin ti Eko, ti wọn wa n pe ni Wesnwọnyan Girls High School, ti ṣiṣi rẹ wá nipasẹ igbiyanju rẹ ni fifun ohun-ini kan ti o ya ile-iwe naa..
wikipedia
yo
Ni ọdun 1913 o da ile-iṣẹ gbigbe ọkọ ayọkẹlẹ akọkọ ni Eko, eyi ti o jẹ anfani Bus Service, o si ni awọn ọkọ nla mẹta, takisí mẹta ati ọkọ akero mefa ti n ṣiṣẹ ni ọdun 1915..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1914, ó dá àjọ Reformed Ògbógbó Frapts sílẹ̀..
wikipedia
yo
wọ́n dà á mọ̀ gẹ́gẹ́ bí ìyá abìyẹ́ àkọ́kọ́, tàbí ọ̀gá obìnrin, ní ọdún kan náà..
wikipedia
yo
Ó kú ní ọdún 1953.Ori-Wkág Phiọ̀túnpists Princessesáwọn Ọjọ́ìbí ni 1874 Loaláìsí ní 1953 Princes Princesces by Marriage of Nigerian Schools and Colleges Women Women Phiṣàánúpi companyrs Womenders in Business unites of sanra Nigeria of Women in Lagos in Lagos From From Lhamuterits 🙂
wikipedia
yo
Amina Temitope Ajayi (A Mama diaspora) jẹ́ ọmọ Nàìjíríà tí ó ń gbé ní Us, àjùmọ̀soro owó tí ó ń kọ ìṣirò, on kòkí àwùjọ àti alákòóso Gapọn agbègbè..
wikipedia
yo
Temitope Ajayi fi ìgbà kan jẹ́ Ààrẹ gbogbo Nigerian American Congress ©
wikipedia
yo
Akitiyan rẹ̀ àti ìtẹ̀síwájú wíwí lórí i Nigerian diaspora ariyanjiyan ti fún ní àkọ́lé tí moniker "Mama diaspora"
wikipedia
yo
Chief Ajayi jẹ mimo gidi nipa sise igbega a ise-ikunni awon obinrin ati mimu iya dópin ni ile Adulawo látara ]
wikipedia
yo
Látara Ìdókòwò ó gbèlé-Nigeria fọ̀rànmú àti àwọn fọ̀rànmú ìpínsímeji ọrọ̀ ajé ní Us, ìdúróṣinṣin àti òdodo O Chief Àjàyí ti jẹ́ ohun-èlò ìdánilójú tí ó n fa ọ̀pọ̀ àwọn olókòwò sínú AGR-Business láti Us si Nigeria..
wikipedia
yo
O je oludasile e Nigerian American Agricultural Empowerment program (AlaEP), ti o koni ni Agricultural Empowerment of Farmers, awon obinrin ati odo ni Naijiria lati fi le fi kun ounje lopo ati lati ṣakoso ise fun awon obinrin ati awon odo ninu eka ise agbe..
wikipedia
yo
AlaEP ni ipilẹ ile-iṣẹ ti o n ko awọn agbe ni 'Mechazedzed farming system', bi o ti n dèrò iṣowo-awin, ACcespọ̀pọ̀ ayẹwo si sise ise agbe, ikore ati ipolowo o ọja wọn nílẹ̀ yi ati lókèèrè..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2010, Chief Àjàyí kan sí Ìjọba Àpapọ̀ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti dín owó èlé lórí i àwọn iṣẹ́ àgbẹ̀ kí wọ́n lè yára sí ẹ̀ka iṣẹ́ àgbẹ̀ àti láti dín ìyà kù nínú orílẹ̀-èdè yìí..
wikipedia
yo
Chief Temitope Ajayi jẹ́ aṣojú ìjọba ti Goodwill fún ìpínlẹ̀ e mẹ́tá àti Maryland, USA..
wikipedia
yo
Ajayi jẹ aṣayan aṣoju fun 2014 Nigeria's National Conference ni bi ti o ti jẹ aṣoju fun National Council of Women Societies (NCws) ni Naijiria o tun sise/sin ni Igbimọ O Confab's Agriculture..
wikipedia
yo
Ninu adirẹsi i Chief Temitope Ajayi ninu ipade ọdọọdun ti World Bank Group ati International Monetary Fund, ó jẹ́ mímọ̀ pé "àwọn obìnrin ní ẹ̀ka agbára aláàdáni, àwọn obìnrin ló ń ṣètò ìná owó ní ìẹbi-èdè nítorí pé pé wọ́n mọ̀ nípa ẹ̀ dáadáa jù àwọn okùnrin lọ”. Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Yemisi Ransome-Kuti ni o jẹ ọmọ kan ṣoṣo Ardkarin Azaríun Olusegun Ransome-Kuti mbẹ (ti won yan sipo as oga agba onimo ìpoògùn fun orile-ede Naijiria ni odun 1956 ti o si sise titi di o fi feyin ti ni odun 1951 member of the most excellent order of the British Empire lati owo King George Vi)..
wikipedia
yo
Ẹ̀gbọ́n rẹ̀ Chief Funmilayo Ransome-Kuti ni o jẹ́ ajàfẹ́tọ́ àwọn obìnrin ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni o wà lára àwọn tí wọ́n lọ sọ̀rọ̀ nípa ìgbòmìnira orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lọ́wọ́ àwọn Britẹni.Ransome-Kuti jẹ́ ìbátan obìnrin Fela Kuti, Oroko Kuti, Beko Ransome-Kuti àti Nobel Prize for Literature Wole Soyinka, ti iya rẹ naa jẹ́ Ransome-Kuti..
wikipedia
yo
Yemisi bi omo mẹrin ti Segun Bucknor jẹ́ àkọ́bí rẹ̀ láti ọ̀dọ̀ ọkọ àkọ́kọ́ rẹ̀ (Captain Frederick Oluwọle Bucknor), bákan náà ni ó bí mẹ́ta fún ọkọ rẹ̀ kejì Dr Kunle Soyẹmí – Bola Soyẹmí, ṣeun Soyẹmí àti Eniola SolaYemi..
wikipedia
yo
Látàrí wípé Fela Kuti, Bẹ̃kọ́ Kuti àti Kofìdí Kuti ti ṣaláìsí, Yemísí ni ó jẹ́ olórí ẹbí fún Ransome-Kuti.Ó fẹ̀yìn tì gẹ́gẹ́ bí alága fún Nigerian Network of Non-governmental Organizations (NFMNGO), Àjọ tí ó dá sílẹ̀ fúnra rẹ̀..
wikipedia
yo
Àjọ irú rẹ̀ tí ó jẹ́ àkókò ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó ti ń ṣiṣẹ́ láti mú ìṣọ̀kan bá àwọn àjọ abẹ́lé àti ilẹ̀ òkèrè láti ọdún 1992..
wikipedia
yo
Lásìkò ọdún 1990, ó dá Àjọ "Girl Watch" kalẹ̀, Àjọ tí Ó n Rí sí Ètò Ẹ̀kọ́ Àwọn Ọ̀dọ́mọbìnrin ní Orílẹ̀-Èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2006, wọ́n yàn án sípò olùdámọ̀ràn pataki Civil Society lábẹ́ àjọ World Bank..
wikipedia
yo
Yemisi wa lara awon ikan pataki obinrin ti won ṣapá lati mu idagba-soke ba ise SDCgs léte ati le osi oun igbẹ Aṣọrube láwùjọ.Awon itọgani FemistsNigerian Women Activište-Ransome-Kuti Familyawon Eniyan AapaYear of Birth Missing (Living People)Yorùbá Women Activište
wikipedia
yo
Princess Adenrele Ademola tabi ọmọ-ọba Adenrele Ademola (ti a bi ni ọdun 1916) jẹ ọmọ-ọba kan ni orile-ede Naijiria ati oṣiṣẹ ilera..
wikipedia
yo
Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè gẹ́gẹ́ bíi nọ́ọ̀sì ní ìlú London ní ọdún 1930, ó sì ń ṣiṣẹ́ rẹ̀ lọ nígbà Ogun Àgbáyé Kejì..
wikipedia
yo
Wọ́n fi ṣe orí-ọ̀rọ̀ fún fíìmù àgbéléwò kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́, lọ́dún Ademola, tí àwọn Mípù Film Unit ṣe àmọ́ tí wọ́n ò rí mọ́ báyìí.Àyè rẹ̀ a bí Ọmọ-ọba Adenrele Ademola ní ọjọ́ kejì, oṣù kìíní, ọdún 1916..
wikipedia
yo
Òun ni ọmọ-ọba Olùdàpọ̀ Ademola, tó jẹ́ Aláké ìlú Abeokuta..
wikipedia
yo
Ó dé sí Britain ní ọjọ́ kọkàndínlógún, oṣù kẹfà, ọdún 1935, ó sì kọ́kọ́ dúró sí ilé-ìgbẹ́ West African Students' Union’s ní Camden Town..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1937, ó lọ sí àpérò ọlọ́lá kan ní Britain pẹ̀lú bàbá àti ẹ̀gbọ́n rẹ̀, AdéTokunbo Ademola..
wikipedia
yo
ó lọ sí ilé-ìwé kan ní Somerset fún ọdún méjì.Àwòrán Ademola kan hàn nínú ìwé kan ní ọdún1942 nípa àwọn ajàfẹ́tọ̀ọ́-ọmọnìyàn lágbàáyé lórí BBC..
wikipedia
yo
George Pearson ṣe fíìmù kan nípa rẹ̀, ó pe àkọ́lé rẹ̀ ní, Communication Ademola, amo lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí, a ó rí mọ́.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Olumi Olufunto bádénoch ( /bekk/ Byddi-K; Nee Adegoke; Born 2 January 1980) je gbajumo oselu omo orile-ede Geesi, o je omo ile-igbimo asofin ile Geesi ni ẹkùn idibo saffron Walden lati odun 2017 titi di akoko yii..
wikipedia
yo
O jẹ ọmọ ẹgbẹ oṣelu Conservative Party, o ti fìgbà kan jẹ minisita kéréje fun ijoba-ibile, ẹsin ati adugbo, ati minisita kéréje fun ori-o-jorí, bakan naa o jẹ igba-keji si Liz Truss láàarín ọdun 2021 si 2022..
wikipedia
yo
Awon obi re ti won je omo orile-ede Nigeria bi i bádénoch ni ilu Wibledon ni London..
wikipedia
yo
Ó lo ìgbà èwe rẹ̀ ní Amẹ́ríkà àti ìlú Èkó lórílẹ̀ èdè Nigeria..
wikipedia
yo
Ó padà sí orílẹ̀ ède United Kingdom nígbà tí ó wà lọ́mọ ọdún mẹ́rìndínlógún..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ìmọ̀-ẹ̀rọ kọ̀m̀pútà ní University of Sussex, ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí onímọ̀ ọ̀rọ̀-èrò ní Lonípò..
wikipedia
yo
Bákan náà ló lọ ṣiṣẹ́ ní ilé-ìfowópamọ́ Royal Bank ní orílẹ̀ èdè Scotland gẹ́gẹ́ bí onímọ̀ ẹ̀rọ kọ̀m̀pútà, kí ó tó tún ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí alájọdarí Nicoutts, lẹ́yìn èyí, ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí adarí ní ilé-iṣẹ́ oníròyìn, The Spectator.Lọ́dún 2012, bádéch fìdí rẹmi nínú ìdìbò fún ilé aṣòfin ìpínlẹ̀ London..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ọdún mẹ́ta, ó gbégbá orókè nínú ìdìbò kan náà nílé ìgbìmọ̀ aṣòfin, London Assembly..
wikipedia
yo
Wọ́n dibò yan an gẹ́gẹ́ bi Aṣojú-ṣòfin ti Jffron Walden ninu idibo 2017..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí Boris Johnson di Ààrẹ, (Prime minister) ilẹ̀ gèésì lọ́dún 2019, wọ́n yan bádénoch gẹ́gẹ́ bí Mínísítà fún ètò àwọn Ọ̀jẹ̀ Wẹ́wẹ́ lábẹ́ ìṣàkóso Akọ̀wé kékeré fún ilé iṣẹ́ elétò àwọn ọmọ wẹ́wẹ́ àti ètò ẹbí..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn èyí, wọ́n yan án gẹ́gẹ́ bí akọ̀wé alámójútó exchekàmàmà secretary to the ilawesury àti parpersonantary under-secretary of state for equalities lọ́dún 2020..
wikipedia
yo
Lọ́dún 2021, wọ́n yàn án ní Mínísítà Kéréje fún Ìjọba-ìbílẹ̀, ẹ̀sìn àti àdúgbò, àti Mínísítà kéréje fún orí-ò-joríLọ́dún 2022, ó kọ̀wé fipò sílẹ̀ láti du ipò Ààrẹ orílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì lábẹ́ ásìya ẹgbẹ́-òṣèlú Conservative Party, lẹ́yìn tí Ààrẹ-Ana, Boris Johnson kọ̀wé fipò sílẹ̀.Àwọn ìtọ́kasí àwọn ènìyàn alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1980..
wikipedia
yo
Adenike ọ̀ladoṣù ( tí wọ́n bí ní 1994) jẹ́ olùgbèjà fún agbègbè aláìléwu fún àwọn ènìyàn àwùjọ, ó sì tún jẹ́ olùgbéró fún ìdásẹ̀sílẹ̀ ilé-ẹ̀kọ́ fún ojú-ọjọ́ tó tẹ́rùn ní orílẹ̀èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O tun ṣafihan iṣẹ oju-ọjọ ailewu ni awọn apejọ ilẹ okeere ti un Climate Change Conference, World Economic Forum, ati Elevate Festival níṣe Graz-Austria.Ní Oṣù Kejìlá, ọdún 2019, Olado kópa nínú ìpàdé Cop25 ní Spain gẹ́gẹ́ bí i aṣojú àwọn ọ̀dọ́ Nàìjíríà níbi ti sọ̀rọ̀ tó mú àwọn ènìyàn lọ́kàn nípa àyípadà ojú-ọjọ́ níilé Afrika àti bí o ṣe yí àwọn ayé pádà.Ìgbésí ayé rẹ Olado jẹ́ ọmọ Ògbómọ̀sọ́ lati ìlú Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó kàwé ní Government Secondary School, Gàkàràwalàdá, Abuja..
wikipedia
yo
Ó sì tún tẹ̀ síwájú ní ilé-ẹ̀kọ́ Federal University of Agriculture, Marijù níbi tí ó ti gba ipò ìiyì àkọ́kọ́ nínú ẹ̀kọ́ ọrọ̀-ajé ajẹmọ́gbin.ní ọdún 2019, wọ́n yàn án fún ìpàdé àkọ́kọ́ tí ún lórí ọ̀rọ̀ nípa ojú-ò ní New York..
wikipedia
yo
Pẹ̀lú ìdánimọ̀ UNICEF gẹ́gẹ́ bíi ọ̀dọ́ tó ń mú ìyípadà dé bá ìlú, ó ń darí àjọ kan tí wọ́n ń pè ní Tèmiroramate.Ní 2019, wọ́n yàn án fún ìpàdé un Youth Climate àkọ́kọ́ tó wáyé ní New York..
wikipedia
yo
Kò ṣàjẹ́è sí ìgbìmọ̀ UNICEF Nàìjíríà gẹ́gẹ́ bí i ọ̀dọ́ Ayàtọ̀, Ó ń Darí Ìdàgbàsókè Ìbílẹ̀ ti ń ṣe Tèmikúmatemate, tó ń ṣègbé fún ìràpadà Lake Chad àti Ìkópa àwọn ọ̀dọ́ nínú Ìdájọ́lẹ̀agbègbè Aláìléwu fún àwọn ènìyàn àwùjọ nípa Ẹ̀kọ́.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo