cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn igbákejì Gómìnà ìpínlẹ̀ Ẹ̀kìtì tẹ́lẹ̀rí.Àárọ̀ ayé àti Èkó rẹ̀ á bí Olayinka ní ìlú Adó-Èkìtì, Ìpínlẹ̀ Èkìtì..
wikipedia
yo
O kawe ni ile-iwe Holy Trinity Grammar School ni ilu Ibadan, ki o to di wipe o lọ si Oliver Baptist High School, ìpínlẹ̀ Oyo, Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó gba àmì-ẹ̀yẹ Bachelor of Business Administration Marketing àti àmì-ẹ̀yẹ Master degree nínú Public Administration ní ilé-ìwé Central State University, Ìpínlẹ̀ Ohio, orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.Iṣẹ́ rẹ̀ Olayinka bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ pẹ̀lú First Bank of Nigeria PLC ní ọdún 1986..
wikipedia
yo
Ó padà wásẹ̀ ní ilé ìfowópamọ́ access Bank àti United Bank of Africa náà.Ní Oṣù Kẹjọ Ọdún 2002, ó di olórí ẹ̀ka ìfipálélógún Affairs ti United Bank of Africa(UBA), ó tún padà di igbákejì àjọ àwọn ìfipáó Manader fún àwọn ilé ìfowópamọ́ ní ọdún 2002 sí ọdún 2004..
wikipedia
yo
Kò tó dipé àyàn gẹ́gẹ́ bí igbákejì gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkìtì, ó jẹ́ Olorì Co-Ọ̀kọ́rate Affairs ti ilé ìfowópamọ́sí Michobank Transatsára Inc.Ìyàn sípò rẹ̀ lẹ́yìn ìdìbò ọdún 2007, a yan ṣẹ́gun oní, ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú People’s Democratic Party(PDP) sípò..
wikipedia
yo
Èyí mú kí Olayemi àti Kayode Feyemi gbé ọ̀rọ̀ náà sile ẹjọ́ pe awon ni o to sipo naa, leyin odun meta abo, ayo ṣẹgun oni nipo, asì gbe Dr..
wikipedia
yo
Kayode feYemi ti Action Congress of Nigeria(ACN) sipo gomina, eyi mu ki Ayan Olayemi gegebi igbakeji oun ni obinrin keji ninu itan lati de ipo igbakeji gomina ipinle Ekitiiku re Olayinka fi aye sile ni 6 April 2013, okunfa iku re ni aarun kogbógun cancer, a sin si Ipinle Ekiti o fi oko re ati awon omo meji sáyé.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Yetunde Oanuga (ti a bi ni 11 September 1960) jẹ Oriku oloselu ni Naijiria ati Igbakeji Gomina ipinlẹ Ogun tẹlẹri.aye rẹ a bi onanuga ni ile iwosan AdeOyo, ilu Ibadan, olu-ilu ipinle Oyo, orukọ baba rẹ ni FaBamwo o kọkọ kawe ni ipinlẹ Ogun ko to dipé o kawe ni ilu Eko nibi to ti gba owe ẹri fun ise olukọni..
wikipedia
yo
Ó padà tẹ̀síwájú láti gba àmì-ẹ̀yẹ mba ní Yunodatì Ìpínlẹ̀ Ògùn..
wikipedia
yo
Oun sise pelu ijoba ipinle Eko lori oro adugbo nigba ti a yan lati dije pẹlu Ibikunle amosun ni ọdun 2015..
wikipedia
yo
Igbakeji Ibikunle Aroko nigba saa akoko re ti Jja si egbe oselu miran, amosun yan onanuga larin awon meta.A yan onanuga sipo eto gomina labẹ egbe oselu APC.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Victoria AdeJoke Orelope-Adefulire (ti a bi ni ojo kokandinlogbon osu Kesan-an, odun 1959) je oloselu ni orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
O jẹ igbakeji gomina ipinle Eko tẹlẹri lati odun 2011 si odun 2015..
wikipedia
yo
Kó tó di pé ó wọlé gẹ́gẹ́ bíi igbákejì gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó, òun ni ó jẹ́ Komisona fún Ẹ̀tọ́ Àwọn Obìnrin ati Ọ̀nà lati mu Iṣẹ́ Pooora Láàárín Ọdún 2003 sí ọdún 2011.Èkó rẹ̀ ó lo ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti Salvation Army ní Agege, ní Ìpínlẹ̀ Èkó láàárín ọdún 1965 sí 1971..
wikipedia
yo
Ó sì tẹ̀síwájú láti lọ ilé-ìwé girama, ó lọ sí St Joseph's Secondary School, máńgòrò tí ó wà ní Ikeja, ìpínlè Èkó ó lo Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Èkó(LASU) láti tẹ̀síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ nibi tí ó ti gba àmì-ẹ̀yẹ Bachelor degree nínú ìmọ̀ Socioloyaya rẹ̀ ọmọ ọba Orelope, tí a bí sínú ìdílé oyè ti ọmọba kakà-laka ti Akeja Oniyanru..
wikipedia
yo
Oun ni obinrin akọkọ laarin ọmọ mẹtala Orelope-Adefuire ti ọpọlọpọ mọ si “Iya alãnú” O sise pelu ile-iṣẹ pZ Industries PLC.Iṣẹ rẹ Orelope jẹ oloselu, nigba ti o kọkọ bẹrẹ oṣelu ,a yan an si House of Assembly ni ipinlẹ Eko, lati se asoju agbegbe apa Alimosho kìíní, kọ pe, ko jinna, wo hn sọ ọ di alaga ile naa..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2022, a yan an gege bii Alaga idibo ti ẹka ipinle Eko.Láàárín ọdun 2003 si ọdun 2007, a yan an gege bii Komisona Eko fun Oro obinrin, o tun dipo naa mu láàarín ọdun 2007 si ọdun 2011..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2011, a yàn án gẹ́gẹ́ bíi igbákejì Gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó, ó sì dípò náà mú títí di ọdún 2015àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ecole nationale de La Statistique et de l'Administration collarque (ensa) jẹ Yunifasiti Aladani ni Ilu Parisi ní Fránsì.Olókìkí Graduates Marc fleurbaey, jẹ́ oludokoowo ajé Faranse ti o se pataki ni ajẹ ti Ilera ati aje ajeji Fránsì..
wikipedia
yo
Bahia ohùn (ti a bi ni ọjọ ketalelogun Oṣu Kẹjọ ọdun 1979) jẹ oṣere tẹnisi alamọdaju orilẹ-ede Morocco tẹlẹ..
wikipedia
yo
Iṣẹ rẹ jẹ ti gbe de ipo No.139, ti o gba ni ọjọ kẹrinlelogun Oṣu Kẹfa ọdun 2002..
wikipedia
yo
O jẹ elere idaraya ti o ga julọ ni ipo ti orilẹ-ede Morocco.ìgbésíayé Abramu jẹ oṣere orilẹ-ede Morocco obinrin akọkọ lati ṣe ifihan ni idije Grand Sider kan ..
wikipedia
yo
ó pàdánù ní ìpele àkọ́kọ́ ti 2002 Australian Open àti 2003 French Open sí ọ̀wọ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Spain Anabel Medina Garrigues àti Czech Zuzana Ondrášková, ni àtẹ̀lé.ninu iṣẹ́ rẹ̀, gbangba gba àmì ẹ̀rí ITF Women's Circuit mọ́kànlá ní ti dádáwá àti mẹsan ti ti eleeyanmeji.O tun gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìdíje ní Irin-ajo WTA, o tun gba ami- ẹri goolu mẹfa ni ere Pan ati goolu kan ni ere Mẹditarenia Mẹditarenia, nigbati o nsoju orilẹ-ede Morocco..
wikipedia
yo
Oríire ise nla ti Mouthassine wa ni Grand Prix SAR La Princesse Lalla Meryem ni Casablanca ni ọdun 2004..
wikipedia
yo
O naa Katarina Srebotgen Eni-kẹta ti o da jù, ti o wa ni ipo 183 ti o fi julo soke rẹ, ni awon eto ere idaraya..
wikipedia
yo
O tun ti lu Sania Mirza ni ITF ni Rabat ni ọdun 2004.Bahia ti fẹyìntì lehin ti o padanu ni ipele akoko ti 2007 Grand Prix SAR La Princesse Lalla Meryem si Vania King .It Ìtọ́kasí awọn Ọjọ́ìbí ni 1979awọn Eniyan AAlààyè
wikipedia
yo
Folashade Sherifat Jaji (ti a bi ni ọjọ keta oṣu Kẹta ọdun 1957) jẹ oṣiṣẹ ijọba ati akọwe fun ijọba ipinlẹ Eko..
wikipedia
yo
Ó tún jẹ́ akọ̀wé fún ìjọba ẹ̀kọ́ lórí ẹ̀ka tó un rí sọ̀rọ̀ owó fún àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba tó ti fẹ̀yìntì..
wikipedia
yo
O ran ijoba orile-ede Naijiria lowo lati mu iyipada rere ba owo ti a fi pamọ fun ilo awon osise ijoba.Àárọ̀ aye ati eko re a bi Sherifat ni March 3, 1957 ni Surulere, ipinle Eko, orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
O lo ile-iwe primari ni ile-iwe Anglican girls Primary to wa ni Surulere, Ipinle Eko kòtò dipé o lọ si Queen's College ni Yaba, nibi to ti gba iwe ẹri WaEC ni ọdun 1974..
wikipedia
yo
O gba ami-eye Bachelor of Science ní Fititì Ilu Ìbàdàn, kò tọ dipé ó lọ sírun ìlú(Agucs) ní ọ̀kan lára àwọn ilé ọti ni Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O tun pada lo si Yunifasiti ilu Eko fun ami-eye master of Business Administration ni odun 1989.Iṣẹ re Sherifat bẹrẹ iṣẹ ijọba ni October 27, 1980 kòtò Didi o bẹrẹ si un sise ni ofici Gomina ipinle Eko, o sise ni ofici Gomina fun odun meji(1980-1982), o ya si ẹka ise ijoba miran koto dipe o tun pada si un sise ni ofici Gomina fun odun meje(1992-1992) March 1, 2011, o di Akowe fun Ijoba Eko ni ẹka to un ri si owo osise feyinti..
wikipedia
yo
Ni March 30 2019, a yan gegebi Akowe Gbogbogbo Ijọba Ipinle EkoAwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Women of Owu jẹ́ ìwé 2006 ti Femi Osofisan kọ àti ti a gbejade nípasẹ̀ Oxford University Press PLC..
wikipedia
yo
Ìwé náà tí a mú láti inú Euripides' The Trojan Women, àpapọ̀ àwọn akọrin, orin àti ijó láti ṣe àfihàn ìtàn àwọn ènìyàn ìjọba Òwu lẹ́hìn tí àwọn ológun ti Ifẹ̀, Ọ̀yọ́ àti Ìjẹ̀bú ti yabo ìlú Òwu fún ọdún méje tí wọ́n pa gbogbo wọn..
wikipedia
yo
ti àwọn oniwe-akọ olugbe ati àwọn ọmọ.Àwọn ìjápọ látìta Review from publisher..
wikipedia
yo
Sarah ADEBIS Sosan jẹ́ olukọni tẹ́lẹ̀ rí ati Igbakeji Gomina Eko laarin ọdún 2007 si 2011 nigba ti Babatunde Fashola je gomina ipinle Eko.ipilẹ a bi Sarah si ipinlẹ Eko ni 11 fèbuary 1956 sinu idile Oloye ati Ọmọọba durosinmi ti ilu irewe ni agbegbe ijọba ibilẹ Ojo, BadaGary..
wikipedia
yo
Ìyá rẹ̀ jẹ́ Ọmọọba ìta-ókè ní Idumota, Èkó, bàbá rẹ̀ sì jẹ́ ọmọọ̀ ẹgbẹ́ òsèlú Action Group(AG) àti Unity Party of Nigeria(UPN), nítorí pé ìyá rẹ̀ jẹ́ ọmọ ọba, Sarah náà gba orúkọ “Ọmọọba”. rẹ̀ ó bẹ̀rẹ̀ ìwé rẹ̀ ní ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ Christ Assembly, Apapa àti ìwé girama rẹ̀ ní Awori-àjérọ̀mí..
wikipedia
yo
Ó tẹ̀síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní Lagos State College of Education, Daríkin (tí a ti yí orúkọ rẹ̀ padà sí Adéníran Ògúnsànyà College of Education) ní ọdún 1980 níbi tó ti gba ìwé-ẹ̀rí nce, lẹ́yìn náà, ó lọ Yunifásítì ìlú Èkó, akọ́kà, níbi tí ó ti gba àmì-ẹ̀yẹ Bachelor of Arts ní ìmọ̀ èdè Òyìnbó ní ọdún 1988, ó sì gba àmì-ẹ̀yẹ Master degree nínú ẹ̀kọ́ àgbà ní ọdún 1989.Òṣèlú láàrín ọdún 1990 sí 1999, sọ fi iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi olùkọ́ni kalẹ̀ láti ṣiṣẹ́ ní Ẹ̀ka ìjọba Ìpínlẹ̀ Èkó, gẹ́gẹ́ bíi òṣìṣẹ́ tó ń rí sọ́rọ̀ Èkó..
wikipedia
yo
Gomina Babatunde Fashola pada yan an gege bii igbakeji re ni odun 2007.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Biodun Stephen je oludari fiimu Naijiria kan, onkowe ati olupilẹṣẹ, ti o se amọja ninu ere ere Ife ati awon fiimu aláwàdà..
wikipedia
yo
O ti ṣe akiyesi fun gbigba awokose fun akọle awọn fiimu rẹ, lati awọn orukọ kikọ akọkọ bi a ṣe fihan ninu fiimu pẹlu "Tiwa Bsábáàtìge" , "Ovy's Voice" ,“Ehi's bitters" ati "Sobi's Mystic" gẹgẹbi awọn apẹẹrẹ akiyesi.Bi o ṣe kẹ́kọ̀ọ́st Stephen jẹ ọmọ ile-ẹkọ giga ti Yunifasiti Obafemi Awolowo, nibiti o ti kọ ẹkọ imọ-jinlẹ..
wikipedia
yo
Lẹhin eyi, o gba ikẹkọ fiimu ni Ile-ẹkọ fiimu Fiimu London (London Film Academy).Iṣẹ fiimuBiodun Stephen bẹrẹ iṣẹ ṣiṣe fiimu rẹ ni ọdun 2014, pẹlu ..
wikipedia
yo
Fíìmù náà ní Ìyìn fún sìmẹ́ǹtì tí ó kéré Síbẹ̀síbẹ̀ ti oyè, bákan bi ìtàn àti ìpilẹ̀ṣẹ̀..
wikipedia
yo
O gba yiyan meji ni 2016 Africa Magic Viewers Choice Awards ni Eko..
wikipedia
yo
lakoko ifọrọwanilẹnuwo pẹlu Tribune lori ọpọlọpọ àwọn ẹya ti iṣe rẹ, o ranti pe iṣẹ iṣẹ ni “Ife akọkọ” rẹ, ṣugbọn kò ni àṣeyọrí ninu rẹ nitorinaa ìpinnu rẹ lati ni ilọsiwaju nipasẹ nini awọn ọgbọn tuntun ni okeere..
wikipedia
yo
O ṣapejuwe ìpèsè ìpìlẹ̀ kan lati ṣe ibaraẹnisọrọ pẹlu agbaye bi iwuri rẹ fun lilo sinu ṣiṣe fiimu..
wikipedia
yo
ní 2017, fiimu Stephen, “Picture Perfect” gba àwọn ìpinnu márun, ó sì gba àwọn àmì-ẹ̀rí méjì ní 2017 Best of Nollywood Awards, fún àwọn ẹ̀ka òṣèré tí ó dára jùlọ ( Boláńlé Nọbalọ́wọ́ ) àti lílo oúnjẹ tó dára jùlọ nínú fiimu..
wikipedia
yo
Ó tún gba ààmì olùdarí tí ó dára jùlọ ní 2016 Maya Awards Africa..
wikipedia
yo
Nigbati o ba sọrọ si iwe iroyin Guardian lori ipilẹṣẹ ti awọn itan ifẹ rẹ, Stephen sọ pe “Mo FA àwòkọ́ṣe lati awọn iriri mi, awọn irora mi, awọn ayọ mi, awọn akoko ibanujẹ ninu igbesi aye mi ati ni igbesi aye awọn eniyan ni ayika mi”
wikipedia
yo
fún ipa oludari rẹ̀ ní tiwa's Bìrẹ́pọ̀ge, o yan fun oludari ti o dara julọ ni "2018 City People Movie Awards" ..
wikipedia
yo
ní oṣù kẹjọ ọdún 2018, fíìmù rẹ méje àti àwọn ọjọ́ ìdajì jẹ́ iṣeduro nípasẹ̀ olùtọ́jú bi fiimu kan lati ríi ni ipari ọ̀sẹ̀..
wikipedia
yo
nínú ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò pẹ̀lú Nigerian Tribune, Stephen rántí pé yíyàn fún AMVCA ti jẹ́ àkọ́kọ́ tí ó ṣe àṣeyọrí jùlọ, ó sì fún u ní ìgboyà láti tẹ̀síwájú ṣíṣe fíìmù..
wikipedia
yo
O ṣe apejuwe Emem Isong ati Mary Njoku gẹgẹbi awọn ẹni-kọọkan laarin ẹka fiimu ti o ṣe iwuri fun u..
wikipedia
yo
iṣẹ́-ọnà rẹ̀ ni níní díẹ̀ nínú àwọn ohun kíkọ títúlar ti jẹ́ àfihàn nípasẹ̀ àwọn aláríwísí fíìmù.Yàtọ̀ sí ṣíṣe fíìmù, Stephen tún jẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́, níbití ó ṣe ìdáwọ́lé ìfihàn ìparí ọ̀sẹ̀ kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Whispers .Àwọn ìtọ́kasíàwọn ọmọ YORÙbáÀwọn ará NaijiriLórí ènìyàn aláàyè..
wikipedia
yo
Kehinde Kamson, ti awon miiran mo si Kjw(a bi ni ojo kerinla osu kejo odun 1961 ni ipinle Eko, Naijiria) je onisowo ati Olùfinitain omo Naijiria..
wikipedia
yo
Òun ni olùdásílẹ̀ àti olùdarí ilé-iṣẹ́ Sweet Sensation Connìkanṣérì Limited, ilé-iṣẹ́ náà jẹ́ ọ̀kan lára a won ilé-iṣẹ́ tó un ṣe oúnjẹ Àtètè ṣẹ̀(fast Food)..
wikipedia
yo
Samson bẹ̀rẹ̀ ilé-iṣẹ́ náà lẹ́yìnkùlé rẹ̀ kò tó dipé ilé-iṣẹ́ náà di gbajúmọ̀.Àárọ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ a bí Kehinde sínú ìdílé Adeleke Beniah Adelàjà(baba rẹ̀) àti ọmọba Adebayo evengelin Adelàjà(ìyá E)..
wikipedia
yo
Baba rẹ̀, Adéfin gbaj Adélàjà jẹ́ ọ̀kan lára àwọn gbajúmọ̀ adarí ilé-ìwé CMS Grmer School - grammer School ti àkọ́kọ́ dálé ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ìyá rẹ̀ jẹ́ adarí Eva Adélàjà Secondary School ní ìpínlẹ̀ Èkó..
wikipedia
yo
Kehinde ati ibeji rẹ jẹ àbíkẹ́yìn baba ati iya wọn ninu ọmọ mẹfa..
wikipedia
yo
O lo ile-iwe International Women's Society Nursery School fun iwe akobere ko to lo staff school ti Yunifasiti eeko fun eko primari re, o ka iwe sekondiri ni ile-iwe St..
wikipedia
yo
Ìgbà tí ó wà ní ilé-ìwé sekondiri ní Ayan láti ṣe aṣojú ilé-ìwé rẹ̀ ní eré ìdárayá All African Games, ó jáwé olúborí nínú àwọn ìdíje títí ó fi ṣe aṣojú ìwọ̀-oorun Afrika..
wikipedia
yo
Ó gba àmì-ẹ̀yẹ Goldu(wúrà) nítorípé ó ṣe aṣojú ìwọ̀-oòrùn Áfríkà nínu eré ìdárayá ti table Tennis bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé ó fìdírẹmi..
wikipedia
yo
Ó gba àmì-ẹ̀yẹ Bachelor degree nínú ìṣirò láti Yunifásítì ìlú Èkó, Nàìjíríà ó tún padà lọ ilé-ìwé ìṣòwò ti Èkó.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
fọ́gu Alakija tí a bí ní Ọjọ́ karùndínlógún Oṣù Keje Ọdún 1951) jẹ́ onisowo àti Olùkòwé ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó ń ṣe ọwọ́ àwọn ikán ọ̀ṣọ́(fashion), epo rọ̀bì, àti ilé títà..
wikipedia
yo
Oun ni Oludari Rose of Sharon Group ati Igbakeji Alaga Confafa Oil Limited gege bi okan lara awon atẹjade Ile iroyin Forbes nipé oun ni obinrin to lowo julọ ni Naijiria, owo rẹ to BilỌpẹ́has kan Dollar ní ọdún 2020.Àárọ̀ aye ati ẹkọ rẹ a bi Alakija ni 15 July 1951 sí Ìdílé Olóyè l..
wikipedia
yo
Alakija lo ile-iwe akobere ti our Ladies of Apoles, ipinle Eko laarin odun 1955 si odun 1958..
wikipedia
yo
Nígbà tó jẹ́ ọmọ ọdún méje, ó lo orílẹ̀-èdè United Kingdom láti tẹ̀síwájú ìwé primari rẹ̀ ní DiOrbem School for Girls laarin ọdún 1959 sí 1963..
wikipedia
yo
Nígbà tó pàrí ẹ̀kọ́ primari rẹ̀, ó lo Muslim High School ní Sagamu, ìpínlẹ̀ Ògùn, kòtò tún padà sí pitman's Central College ní Londonise rẹ̀ Aladara bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní ọdún 1974 gẹ́gẹ́ bí akọ̀wé ilé-iṣẹ́ àìpànìyàn (Adev ní ìpínlẹ̀ Èkó..
wikipedia
yo
O pada lo sise ni ile ifowopamo ifowopamo first National Bank ti Chicago gegebi Akowe fun adari ile ifowopamosi naa..
wikipedia
yo
Nitori ifẹ rẹ si Oge ati Ogun, o lo ile-iwe kan ni London lati kọ nipa aṣọ rírán, nigba ti o pada si Naijiria, o bẹrẹ ile-iṣẹ oso rẹ ti o pe ni Supreme stidara, o pada yi orukọ rẹ pada si Rose of Sharon House of Fashion ni odun 1996.ififuni Alakija da Rose of Sharon Foundation kale lati ran awon opo ati omo alaini baba ati iya lowo nipa ṣiṣan owo ile-iwe won ati fifun won lowo fun oko owo.Ìdílé rẹ Alakija fe agbejoro, Moroko, Moroko lati idile Adeja Alakija ja ni osu Kọkànlá, odun 1976..
wikipedia
yo
Àwọn méjèjì ún gbé ní ìpínlẹ̀ Èkó pẹ̀lú ọmọ wọn mẹ́rẹ̀rin àti Ọmọ-ọmọ wọn.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
AdéFunmilayo Tejuosho (orukọ àbísọ rẹ̀ ní Smith) tí a bí ní ọjọ́ karùndínlọ́gbọ̀n Oṣù Kàrún ọdún 1965 jẹ́ ìgbòsí olósèlú ní Nàìjíríà, ó tún jẹ́ aṣojú agbègbè ní ní House of Assembly Ìpínlẹ̀ Èkó, òun ni alága House of Assembly Èkó tí ó ún rí sí ètò owó.Àárọ̀ ayé àti Èkó rea bí Stoté ní Ìpínlẹ̀ Èkó sí Ìdílé Ademola Smith, Lo ilé-ìwé primari ti Yunifásítì ìlú Èkó, ó lo ilé-ìwé Queens College fún ìwé sẹ́kọ́ndírì, Èkó ó parí ìwé mẹ́rin rẹ̀ ní West Virginia, lẹ́yìn ìwé rẹ̀, ó tẹ̀síwájú láti gba àmì-ẹ̀yẹ nínú ìmọ̀ bí ní Yunifásítì ti West Virginia..
wikipedia
yo
Ó padà gba àmì-ẹ̀yẹ nínu ìmọ̀ òfin ní Yunifásítì ti BuUC..
wikipedia
yo
tẹnuous gba ami-eye Ph.D ninu imo ofin lati Yunifasiti ti ilu Eko.Iṣẹ rẹ̀nígbà ise AguTọ́rọ̀ re, O sise ni ile-iwe Queens College tí o ti jáde..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2003, a yan Psí láti sojú House of Assembly Ìpínlẹ̀ Èkó, nígbà tó wà ní́ì náà, ó mú àbá òfin wá láti dojukọ́ ọkọ níná ìyàwó àti ìyàwó nína ọkọ..
wikipedia
yo
Àbá náà padà di òfin.Ìdílé rẹ̀ó fẹ́ ọmọba Káyọ̀dé Tejuosho ti ìdílé Adé Tejuosho ìpínlẹ̀ Ògùn , Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Felicia Eze jẹ́ agbábọ́ọ̀lù lobinrin orílẹ̀ ède Naiigiria tí a Bìní 27, Oṣù September ní ọdún 1974..
wikipedia
yo
Arábìnrin náà kú lẹ́yìn àìsàn ránpẹ́ ní 31, oṣù January ní ọdún 2012 sí ìpínlẹ̀ Anambra.ÀṣeyọríFelicia Gẹ́gẹ́bí ọ̀kan lára ọmọ ẹgbẹ́ Super falcons gba àmì ẹ̀yẹ Gold ní ọdún 2003 níbi gbogbo Game Ilé Àfimíràn fún NAIGria, Arábìnrin náà kópa nínú Olympic ọdún 2004 níbi tí ó ti sojú orílẹ̀ èdè NAATria.Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ulunma Jérôme je agbaboolu obinrin orile ede Naijiria ti a bi ni ojo Kọkànlá osu kerin odun 1988..
wikipedia
yo
Ó ń gbá bọ́ọ̀lù jẹun gẹ́gẹ́ bi adilémú lọ́wọ́Bẹ́yin fún ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù Pitea tí ó wà ní Sweden Damallsvenskan.CS1 ti kópa nínu pẹ̀lú oríṣiríṣi eré fún Team àwọn obìnrin ti National lórí bọ́ọ̀lù bọ́ọ̀lù..
wikipedia
yo
Tawa Ishola jẹ́ agbábọ́ọ̀lù lobinrin orílẹ̀ ède Nairia tí a Bìní 23, Oṣù December ní ọdún 1988..
wikipedia
yo
Arabinrin naa ṣere gẹgẹbi midfielder fun team awọn obinrin ti National lori bọọlu.aṣeyọrielere naa kopa ninu Olympic ọdun 2008 nibi ti o ti arabinrin naa ṣoju fun naigiria.itọkasi..
wikipedia
yo
Lilian Cole jẹ agbabọọlu lobinrin orilẹ edè naigiria ti a bini 1, oṣu August ni ọdun 1985..
wikipedia
yo
Arabinrin naa ṣere gẹgẹbi Defender fun apapọ team awon obinrin ile naigiria lori bọọlu.aṣeyọrikórìíra kopa ninu Olympic ọdun 2008 nibi ti o ti ṣoju orilẹ edè naigiriaitọkasi..
wikipedia
yo
Tawa Ishola ti a bi ni ọjọ ketalelogun Oṣu kejila ọdun 1988 jẹ agbabọọlu afẹsẹgba ti orilẹ-ede Naijiria kan ti o gba bọọlu lọwọ aarin fun ẹgbẹ agbabọọlu obinrin agba orilẹ-ede Naijiria ni Olimpiiki ni ọdun 2008 .wo eyi naa orilẹ-ede Naijiria ni Olimpiiki Igba ooru 2008àwọn itọkasiita ìjápọ Profile at Sports-Reference.com Eko Ishola at Soccerway Ọdun Ẹlaaye Ọjọ́ìbí ni 1988..
wikipedia
yo
Salem Fthi elmslaty (ti a bi ni ọjọ kankanlelogbon oṣu Kẹwa Ọdun 1992), oorul a le ko ati sipeli bi Salem Al-Musallati ati ti a mọ ni ibigbogbo bi Salem Roma, jẹ agbabọọlu Libyan kan ti o n gba bọọlu fun Al-Nasr gege agbabọọlu agbaowojun .Iṣẹ oke'ere Awọn ikun ati awọn abajade se atokọ awọn ibi-afẹde ifiyesi ni akoko.Awon Ife rẹ Al-Nasr 2016 Libyan Premier League ti o gba goolu goolu mẹjọ wọle ti o si fi gba eniti o gba goolu ti o pọju lo.Awon itọkasi awọn eniyan Apeawọn Ọjọ́ìbí ni 1992..
wikipedia
yo
Ngozi ọkọbi jẹ́ agbábọ́ọ̀lù lobinrin orílẹ̀ ède Naiigiria tí a Bìní 14, Oṣù December ní ọdún 1993..
wikipedia
yo
Arabinrin naa ṣere fun Swedish Club Eskilstuna United Dff gegebi ipo Forwardaṣesoringozi kopa ninu FIFA U-17 Cup awon obinrin agbaye ni odun 2008, 2010 ati FIFA U-20 Cup awon obinrin Agbaye ni ọdun 2012 nibi ti o je asoju team awon obinrin apapo ile naigiria lori bọọlu.Ngozi kopa ninu ere idije awon obinrin ile afizko ni ọdun 2010, 2012 ati 2014.itọkasi..
wikipedia
yo
Glory iroka je agbaboolu lobinrin orile ede naigiria ti a bini 3, osu January ni ọdun 1990..
wikipedia
yo
Arabinrin ṣere fun River Angels ati team awọn obinrin apapọ ile naigiria lori bọọlu gegebi midfielder.aseyoriglory kopa ninu ere idije awon obinrin Ike afirica ni odun 2012 ati 2014 nibi ti o ti yege.itọkasi..
wikipedia
yo
Àdánna Nwanẹ̀ri jẹ agbabọọlu lobinrin orile ede naigiria ti a bini ọjọ 31, oṣu August ni ọdun 1975..
wikipedia
yo
Arabinrin naa ṣere gẹgẹbi Defender fun team awon obinrin apapo ile naigiria lori bọọlu.aṣeyọrina wa lara awọn agbabọọlu ti o kopa ninu FIFA Cup awọn obinrin Agbaye ni ọdun 1999.itọkasi..
wikipedia
yo
Ogoipa Chukwudi je agbaboolu lobinrin orile ede naigiria ti a bini 14, osu September ni odun 1988..
wikipedia
yo
Arabinrin naa ṣere fun Italian Club Lazio ati apapọ team awọn obinrin gegebi midfielder.aṣeyọriogofìtílà kopa ninu FIFA Cup awon obinrin agbaye ni ọdun 2011 nibi ti o ti ṣoju orile ede naigiria.itọkasi..
wikipedia
yo
Àwọn ènìyàn bwátí ti wọn n pe ni Bago ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn ti o le ríi ni numan, demsa ati lamur àwọn ìjọba ìbílẹ̀ ni apá Gúsù ti Ipinlewa Adamawa ati ni die ninu àwọn orílẹ̀-èdè Cameroon. ipilẹṣẹ ipilẹṣẹ àwọn ènìyàn bilẹ̀ Boke le se to kuro lati ọdọ àwọn ènìyàn Gobir..
wikipedia
yo
Gẹgẹbi itan, àwọn eniyan Gobir ti o gba agbegbe Niger ati diẹ ninu awọn ariwa iwọ-oorun Naijiria..
wikipedia
yo
Wọ́n jẹ́ alágbára àti akọni nítorí agbára wọn àti àwọn ọgbọ̀n ní ogun àti iṣẹ́ ọnà..
wikipedia
yo