cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Àjọ UNESCO sọ ibẹ̀ di World World Heritage site ní ọdún 1988..
wikipedia
yo
Lóde òní, ìlú Medina ní ilé Natasha Archaeological Museum of Soísún Wa.Ìtani Median ti Soíàṣẹ ni ó wà ní yèwó Sahel tí ó sì ní àwọn ilé àwòdamiẹnu tí wón dá dúró tí wọ́n sì dá yàtọ̀, èyí rí bẹ́ẹ̀ látàrí wọ́n ti kọ́ àwọn ilé wọ̀nyí láti ìgbà tí ọ̀làjú ẹ̀sìn Islam kọ́kọ́ dé ni , èyí ni ó fi jẹ́ kí ó wà lára àwọn ilé tí ti pé jùlọ nínú ìtàn tí ó sì tún sọ bí ìtàn ẹ̀sìn Islam ṣe tàn ká..
wikipedia
yo
Ìdí tún ni wípé ìlú Medina nílò ààbò tó péye lọ́wọ́ àwọn adàlúrú àti àwọn olè nígbà náà .Ìsọ̀wọ́ gbé ilé kíkọ́ kalẹ̀ ní ìlú náà fi bí ọ̀làjú tí ẹ̀sìn Islam mú wá nígbà náà tí láyéòde oní nlbí ó ṣe lágbára tó..
wikipedia
yo
Àwo ọ̀nà àti ọnà ìdílé nígbà YèèLY ni ó fi hàn wípé wọ́n mú lele lórí ààbó nípa kí ilé iso fún àwọn ọmọ ogun láti lè dojú kọ àwọn ọjẹ̀̀ tàbí ọ̀gbẹ tí wọ́n bá fẹ́ kọ lu wọn.Awon Irisí sí Oríjà in tunis in ṣẹ̀yìn in tunis in tunis in Kalas..
wikipedia
yo
IChan Kala () ilu ti won reti yika ti o wa ni khival ni USbephile ilu yi ti wa labẹ inojuoju ati idaabobo ajo World Heritage site lati ọdun 1990..
wikipedia
yo
Ìlú àtijọ́ yí ní àwọn ibi ìtàn ní àgbáyé tí ó tó àádọ́ta tí wọ́n sì ti wá láti ọ̀rúndún kejìdínlógún tàbí kọkàndínlógún sẹ́yìn..
wikipedia
yo
Fún àpẹẹrẹ, mọ́ṣáláṣí dmámá ni wọ́n kọ́ ní àárín ọ̀rúndún kẹwàá tí wọ́n sì tún mọ́ṣáláṣí náà kí ní ọdún 1788 sí 1789.Ohun tí ó ṣe pàtàkì jùlọ tí ó fiju hàn ní íChan Kala ni àwọn bíríkì alámọ̀ tí wọ́n fi mọ́ géètì yíká ìlú náà..
wikipedia
yo
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé wọ́n ti fi ìpìlẹ̀ ìlú náà lélẹ̀ ní nkan bí ọ̀rúndún kẹwàá tí ó jẹ́ tí wọ́n sì fi ìpìlẹ̀ àwọn odi náà lélẹ̀ ní ààrin ọ̀rúndún kẹtàlélógún tí wọ́n sì tún ṣe láìpẹ́Galleryàwọn ìtọ́ka síàwọn ìjásóde IChan Kala - UNESCO World Heritage CentreArchaeological sites in UzbekistanWorld Heritage sites in Uzbekistanxollem Reginunubẹ̃clays..
wikipedia
yo
Old Town of Prague () níbo jẹ́ ìletò kan tí ó ti wà tipẹ́ ní ìlú Prague, ní orílẹ̀-èdè Czech Republic..
wikipedia
yo
Wọ́n yà á sọ́tọ̀ láti ìta pẹ̀lú odi kẹ̀rẹ̀bẹ̀tẹ̀ kan tí wọ́n pè ní tẹ́júunva tí ó sì ní odo ní apá ọ̀tún àti apá òsì..
wikipedia
yo
Kòtò yí ni wọ́n fi òpópó oríṣiríṣi bò mọ́lẹ̀ láti apá (North sí South-West) Revolucni, na Príkòpe, àti ìyẹn ‘Dni) tí ó sì jẹ́ ààlà fún abúlé Anarake ní Old Town..
wikipedia
yo
Old Town ní àwọn ìlú bíi New Town of Prague yí po..
wikipedia
yo
Nìṣó afárá Odò BRUgvva tí ó sọ Afárá Charles Bridge ní Noth Town of Prague ()..
wikipedia
yo
Ìlú àwọn Júù tẹ́lẹ̀ (Joséfov) nió wà ní apá àríwá Old Town tí ó dojú kọ ìlú ìkọ̀sẹ̀tav.Ìtàn láti ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀, ní nkan bí ọ̀rúndún Kẹ́sà, Stare Mesto ni ó wà ní apá ibi tí ọjà wà nítòsí odò ìkọ̀sẹ̀tava..
wikipedia
yo
Àkọsílẹ̀ tí wọ́n ti kọ sílẹ̀ ní nkan bí ọdún 1100 ad ni ó fi hàn wípé ní gbogbo ọjọ́ Àbámẹ́ta ni wọ́n ma ń nájà, ti ìpàdé àwọn ológun tí wọn kò lóǹkà náà má ń wáyé níbẹ̀ pẹ̀lú..
wikipedia
yo
Àwọn Olúnajá oríṣiríṣi ni wọ́n ti tara ọjà yí lọ́wọ́ lọ́wọ́, àti wípé ob Wences I of Bohemia tún fún wọn ní àǹfàní láti dá ìlú Prague (Mesto PRazayikeki) sílẹ̀..
wikipedia
yo
Gègé àkọsílẹ̀ ayé àtijọ́ ti fi lélẹ̀, ìlú yí ni géètì tí ó tó mẹtala níye , tí ó sì tún ní kòtò ńlá kan yíká ìlú náà láti lè fi ṣe ààbò fún ìlú náà lọ́wọ́ ìkọlù..
wikipedia
yo
ní ọdún 13, ọba ìlú Bohemia iye JHonré of Luxembourg fún alámòójútó abẹ́lé ní àṣẹ láti láti ra ilé ẹbí kan lọ́wọ́ ẹbí Volfin ód Kamerun (), ilẹ̀ tí wọ́n rà yí ní wọ́ n sọ di ilẹ̀ ìlú títí di òní..
wikipedia
yo
Ní nkan bí àárí ọ̀gbun ọ̀rúndún kẹrìnlá, ìlú Old Town bẹ̀rẹ̀ sí ń gbòòrò sí látàrí akitiyan àwọn ọlọ́jà àti àwọn ohun àtinúdá ọgbọ́n inú tí wọ́n pèsè tí wọ́n sì ń tà lọ́jà wọn, èyí mú kí ó di ojúkò okòwò fún àárín gbùngbùn Yúróòpù àti Agb3 rẹ̀.Òkìkí ìlú Old Town ń gbilẹ̀ sí pàá pàá jùlọ nígbà tí Ọba Bohemia Charles IV jẹ́ tí ó sì tún di Roman Emprọ ní ọdún 13, òkìkí yí túbọ̀ túbọ̀ pọ̀..
wikipedia
yo
Látàrí jíjẹ́ ọba yí, àwọn ènìyàn bá ṣíjú sí ìlú Prague tí ó jẹ́ ìlú tí ọba náà ti wá..
wikipedia
yo
Wọ́n tún ilé ìlú náà kọ́ sí pètésì alájá gogoro tí ó ń fi agbára ati ipò pàtàkì ti ọba náà wà hàn lára ìlú rẹ̀..
wikipedia
yo
Nígbà tí àwọn yóò fi parí kíkọ́ ilẹ̀ ìlú náà tan ní ọdún 1364, ilẹ̀ náà ni ó ga tí ó sì rẹwà jùlọ nínú ìlú náà.Lẹ́yìn tí wọ́n fẹ́ ìlú náà lójú síwájú sí, ní ọ̀rúndún kẹrìnlá, tí wọ́n sì ti kọ́ ilẹ̀ ìlú tuntun fún wọn, wọ́n pa gbogbo kòtò tí wọ́n gbẹ́ yíká odi ìlú náà rẹ́ pátá..
wikipedia
yo
Ní ọdún kópa, ni wọ́n dá University of Prague sílẹ̀ láti ọwọ́ Ọba Charles IV..
wikipedia
yo
Ọba yí tún bẹ̀rẹ̀ sí ń kọ New Bridge ní ọdún 13 sórí odò tí ìkọ̀sẹ̀tava tí yóò sọ Old Town pọ̀ mọ́ Nolian Town of Prague..
wikipedia
yo
Ọdún 1391, ni wọ́n kọ́ ilé ìjọsìn Bethlehem Chapel sí Czech..
wikipedia
yo
Ile-ijọsin yi ko ipa ribiribi ninu ìṣàtúnṣe si Bohemian ati Huls movement..
wikipedia
yo
ajíyìnrere Jan Hus ni ó lo ilẹ̀JỌsìn laarin ọdún 1402-14 láti fi ṣe ìwàásù .Iná kan tí wọ́n ń pè ní (French fire) ni ó jà ní ọdún 1689 tí ó sì run ọ̀pọ̀ ohun ìní ní Old Town tí ó fi mọ́ ìlú kan tí ó sún mọ́ wọn tí wọ́n ń pè ní Jewish Town..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1784, àwọn ìlú mẹ́rin tí wọ́n múlẹ̀ ti ara wọn ni wọ́n kóra pọ̀ tí wọ́n ń pè ní Royal Capital City of Prague lábẹ́ ìjọba kan ṣoṣo.Àwọn àwòránàwọn ìtọ́ka ṣíwọ́ èyí náààwọn àyọkà tí a ṣòpò Malé Namesti, a Square in the Old Town Tipects of Prague..
wikipedia
yo
Tallinn old town ránká is the oldest part of Tallinn, Estonia..
wikipedia
yo
Old Town of Tallinn has managed to wholly preserve its Structure of medieval and Handunniati Origin..
wikipedia
yo
Old Town Represents an exceptimudic intact 13th century City Plan..
wikipedia
yo
Since 1997, the area has been registered in the UNESCO World Heritage list..
wikipedia
yo
Its area is 113 ha and there is a buffer Zone of 2,253 ha.The majority of the old town's structures were built during the 13th-16th Centuries.during World War II, Notable destruct took place in 1944 during so-called March bombing ()..
wikipedia
yo
About 10% of the buildings in the old town were destroyed.reOrílẹ̀esexèyíkéyìí abo about old town, Visittallinn.ẹẹ́tamaren old town, www.Visitescasal.com ìyẹ̀funmentsments in Eṣtoniawọrld Heritage sites in EstoniaOld Towclays Tokojú town..
wikipedia
yo
Ìlú Old towns of Ddnne jẹ́ ìlú tí èro pọ̀ sí gidi tí ó wà ní Ddnne, ní orílẹ̀-èdè Málì..
wikipedia
yo
Ọdún 1988 ni àjọ UNESCO fi ìlú yí sí abẹ́ ìbojúwò wọ́n ní World Heritage list.Ìtàn ara ddnne ti ń gbé ìlú wọn láti ǹkan bi ọdún 250 B.C., Ìlú yí tún di ojú ọjà àti ojúkò pàtàkì fún àwọn olùta góòlù..
wikipedia
yo
Ní ọ̀rúndún kẹ́ẹ̀dógún sí ìkẹrìndínlógún sẹ́yìn, ìlú yí jẹ́ ibi tí ẹ̀sìn Islam ti gbilẹ̀ dára dára tí àwọn ènìyàn sì ń kọ nípa ẹ̀sìn náà níbẹ̀..
wikipedia
yo
Púpọ̀ àwọn ilé ATjọ́ tí wọ́n tó ẹgbẹ̀rún méjì tí wọ́n fi àpáta kọ́ ni wọ́n sì wà ní ìdúró títí di òní àwọn ilé náà ni wọ́n pè ní (togu)..)..
wikipedia
yo
Wọ́n kọ́ àwọn ilé náà láti fi dẹ́kun ìṣẹ̀lẹ̀ omíyalé ni .àwọn orísunàwọn itọ́ sí..
wikipedia
yo
Procopius Basilica in TrectifÀwọn Ìtoka sí World Heritage sites in the Czech Republic..
wikipedia
yo
Interlingue, ni Occidental ti o ti kọjá, jẹ́ èdè Olùrànlọ́wọ́ Kariaye tí o ṣẹda nipasẹ nipasẹ Edgar dehl ati ti a tẹjade ni ọdun 1922.Litireso awọn ọrọ iwe-kikọ akọkọ ni Interlingue han ni Comogukaglota..
wikipedia
yo
Àwọn iṣẹ́ kan tún wà, àwọn tí wọ́n jẹ́ ìpilẹ̀ṣẹ̀ àti àwọn tí wọ́n túmọ̀, tí wọ́n tẹ̀ jáde ní Interlingue..
wikipedia
yo
Awon oro miiran han ninu iwe irohin Helvetia sugbon awon wonyi ko wọpọ..
wikipedia
yo
MiCri Chdclayshie jẹ́ apẹẹrẹ ti iṣe ti a tumọ, ti o nfihan akojọpọ awọn ọrọ nipasẹ káàárẹ̀VV Podobs, H..
wikipedia
yo
Àwọn ará ìlú Romania jẹ́ ẹ̀yà Indo-Aryan, àwọn arìnrìn àjò ti àṣà tí ó ngbé púpọ̀ jùlọ ní Yúróòpù, àti àwọn olùgbé ìlú òkèèrè ní Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Romani gẹgẹbi eniyan ti wa lati iha ariwa India, lati Rajasthan, Haryana, ati awọn agbegbe Punjab ti India ode oni...
wikipedia
yo
Sosa Malone je akorin ati Grime MC lati North West London..
wikipedia
yo
Ó wà ní ibùsọ̀ 180 ní àríwá ti Helsinki, olú-ìlú náà..
wikipedia
yo
O fẹ́rẹ̀ tó eniyan 250,000 ńgbé ní Tampere.itọkasi FinlánNA..
wikipedia
yo
Suya tàbí skewer tí àṣà tí àṣà mú skewer tí o wà láti Ariwa Naijiria, ilẹ̀ Hausa àti pé o jẹ́ oúnjẹ tí o gbajúmọ̀ ni Iwọ-oorun Afirika ..
wikipedia
yo
Suya (tún n pe ní Soya) jẹ́ ẹyà nla ninu àṣà ati oúnjẹ Hausa àti itan-akọọlẹ ti pèsè ati ṣe nipasẹ àwọn ọkùnrin Hausa 'Mai nama' (kìí ṣe àwọn obìnrin)..
wikipedia
yo
Suya ní gbogbogbo ni a ṣe pẹ̀lú ẹran màálù, agbo, tabi adiẹ..
wikipedia
yo
àwọn Innards gẹgẹ bi kidinrin, ẹdọ àti tripe tun lọ..
wikipedia
yo
èran ẹ̀gẹ́ tínrín náà ni ao máà fi oríṣìíríṣìí turari, eléyìí tó wà nínú kúkì Ẹ̀ro Ẹ̀pa Ìbílẹ̀ Hausa ti ìbílẹ̀ ti wọn n pe ni 'kwù', iyọ̀, epo ẹ̀fọ́ àti àwọn tùràrí àti adùn miran, ao wá fi bẹbẹyára..
wikipedia
yo
Oríṣṣṣṣ Suya ló wà nínú Ṣíṣe Ṣítún Hausa (gegebi Origugugu, Kādo ati bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ.. ṣùgbọ́n èyí tí ó gbajúmọ̀ jùlọ ni Suya..
wikipedia
yo
Suya ti Wa ni asa pẹlu afikun iranlọwọ ti ata gbigbe papo, ibile Hausa turari ati ki o ege alubosa..
wikipedia
yo
Bákan náà ni wọ́n máa ń ṣe é ní àṣà ìbílẹ̀ Hausa pẹ̀lú ìhà ẹ̀gbẹ́ Hausa Masa (ìrẹsì fermented/ ọkà/àkàrà àgbàdo)..
wikipedia
yo
Awon ona igbaradi ẹran Halal ni a maa n lo nigbagbogbo, paapaa ni awon agbegbe ariwa ti Nigeria nibiti o ti bere gege bi asa pelu awon ounje Hausa ibile, nibiti ifura ti ko ni ibamu si awon Ìdinamo ounje Musulumi ni igbaradi Suya ti je mimo lati fa awon rudurudu..
wikipedia
yo
ó lé jẹ pẹ̀lú Masa, Kosai, Garri tàbí ògì .Kò sí ohunelò tí ó ṣe déédé fun iṣelọpọ tí idapọpọ ẹka ti àwọn turari àti àwọn àfikún èyítí ó jẹ́ Suya marinade (tí a pè ní Yji ) àti Ìdápọ̀ tùràrí tí a ṣiṣẹ́ pẹ̀lú rẹ̀..
wikipedia
yo
Àwọn èròjà lè yàtọ̀ ní ìbámu sí àwọn àyànfẹ́ ti ara ẹni ati agbègbè..
wikipedia
yo
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wí pé Suya jẹ́ oúnjẹ ìbílẹ̀ Hausa tí Nàìjíríà, ó ti gba gbogbo àwùjọ Nàìjíríà láwùjọ, tí o ní owó fún gbogbo ènìyàn àti pé ó wà níbí gbogbo..
wikipedia
yo
Suya tí di mọ́kàndínlógún orílẹ̀-èdè Nàìjíríà pẹ̀lú àwọn agbègbè oríṣiríṣi tí ní sọ pé ó ga jùlọ tí ìlànà wọn àti àwọn ọ̀nà ìgbaradì, ṣùgbọ́n àwọn ìlànà ẹran dídín tí ó jọra ni ó wọ́pọ̀ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè Ìwọ̀-Oòrùn Áfíríkà.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Gari ni ohun jíjẹ lẹ́bú-lẹ́bú kan tí ó ma ń ní àwọ̀ funfun tàbí awọ orí tí wọ́n ma ń ṣe jáde láti ara ẹ̀gẹ́ tí a tún n pè ní pákí..
wikipedia
yo
Irúfẹ́ oúnjẹ yí wọ́pọ̀ ní apá ìwọ̀ oòrùn ilẹ̀ adúláwọ̀..
wikipedia
yo
Oríṣṣiri ohun tí wọ́n sèṣẹ láti ara nkan bíi agbado, ìrẹsì, iṣè tàbí ọkà baba tí wọ́n sì sọ di iyẹfun ni àwọn ẹ̀yà Hausa sábà ma ń pe ní gãga, tí wọ́n yoo si ma fi orúkọ ohun tí wọ́n fi ṣe òránjáde náà kún..
wikipedia
yo
Ẹni tí ó bá wù lè ta epo díẹ̀ si kí àwọnrẹ̀ lè yí padà kúrò ní funfun sí rẹ́súrẹ́sú..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn èyí, wọn yóò kó sínú àpò tí wọn yóò sì lo ẹnu àpò ti wọ̀ yóò sì gbé nkan ńlá tí ó wúwo lée kí omi rẹ̀ ó lè rọ̀ dànù láàrín wákàtí kan sí mẹ́ta..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí ó bá ti gbẹ̀mí tán, wọn yóo jọ̀ọ́ kí wọ́n tó bẹ̀rẹ̀ sí ń yan án lórí iná..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí gàrí babdele tán, a lè gbé pamọ́ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọjọ́ fún lílò ọjọ́ iwájú.Àwọn ohun tí a lè fi gàrí ṣe a lè fi gàrí tẹ ẹ̀bá nígbà tí wọ́n bá dà á sínú omi gbígbóná tí a sì rọ̀ọ́ mọ́ra wọn dára dára kí ó lè lè lọ́wọ́., bákan náà ni a lè fi ẹ̀bá yí jẹ oríṣiríṣi ọbẹ̀ èyí tí ó bá wù wá..
wikipedia
yo
A lè fi ǹgárì ṣe kòkòrò, èyí jẹ́ oúnjẹ ìpanu kan tí a ma ń kàn jẹ tí ó wọ́pọ̀ ní àwọn ìlú bí Ẹ̀gbá tàbí yéwa, ìpínlẹ̀ Ámọ́, Ìpínlẹ̀ Rivers, Ìpínlẹ̀ Anambra àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Oríṣiríṣi ìrísí ni gàrí ma ń ní, ó lè jẹ èyí tí ó kùnà, tàbí kí ó má kùnà, èyíkéyí tí ó bá jẹ níbẹ̀ ni ó ṣe é jẹ bí ońjẹ..
wikipedia
yo
A lè mu gàrí nínú omi tútù nígbà tí a lè fi ṣúgà, oyin, ẹ̀pà àti mílíkì mú u..
wikipedia
yo
Bá kán náà ni a lè jẹ gàrí lásán láì tẹ̀ ẹ́ lẹ́yín tàbí fomi mú u.Oríṣi gàrí tó wàoríṣi gàrí tí ó wá pàá pàá jùlọ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní gàrí funfun àti gàrí pupa..
wikipedia
yo
.Ẹ tún lè wo African Cuisine Simi cassava-based dishes bâb Aroko Ume ògì (Food) poi list of African dishes Teiàwọn ìtọ́ka síàwọn ìtàkùn ìṣẹ́gungari on Ghana.com Igbo Zore on Garri Cuìsìn Cuìsìn Gemi CuTgainesrọ Cuìsìnfífarabalẹ̀ Custaple Foostaple food Leonean CuNítorítí Cuìsìn dishes..
wikipedia
yo
Ẹ̀bà jẹ́ oúnjẹ òkèlè tí wọ́n ma ń jẹ ní apá ilẹ̀ AduIlẹ̀ àti agbègbè rẹ̀ pàá pàá jùlọ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Gánà..
wikipedia
yo
Ẹ̀bà ni àwọn ẹ̀yà Yorùbá sábà ń pèé ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
It is a cooked starchy vegetable Food made from Oríyín grated cassava (manioc) flour, Commonly known as gàrí.Bí a ṣe ń tẹ ẹ̀bá a ó gbé omi ka iná, tí ó bá ti gbóná, a ó da gàrí wá sínú rẹ̀ a ó wá ròó pó dára dára kí ó lè lé lọ́wọ́..
wikipedia
yo
Articles with HcardsLinda Ifeoma Ikeji (tí a bí ní ọjọ́ kọkándínlógún osù Keta an ọdún 1980) jẹ́ òǹkòwé, oníṣòwò, òǹkòwé sínú ìwé ìròyìn ti orí ẹ̀ro-ayélujára àti ẹni tí ó ti jẹ́ aláwòṣe ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Linda jẹ́ ìlú mọ̀ọ́ká nítorí ìwé tí ó ma ńkọ sínú ìwé ìròyìn lórí ẹ̀rọ-ayélujára àti wípé àwọn ìwé kíkọ rẹ̀ yí sábà ma ńdá lórí i àríyànjiyàn.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ àti ẹ̀kọ́ Ikeji ni wọ́n bí tí wọ́n sì tọ́ dàgbà ní ìdílé Kátólíkì kan láti Nk— ìpínlẹ̀ ìmọ̀, Nigeria ..
wikipedia
yo
O kọ ẹkọ jade ni Ile-ẹkọ sekondiri ni ọmọ ọdun mẹ́tàdínlógún..
wikipedia
yo
Nigbati o di ọmọ ọdun mejidinlogun ni o fi orukọ silẹ ni ile-ẹkọ giga Yunifasiti Ilu Eko nibi ti o ti kọ ẹkọ lori ede Gẹẹsi..
wikipedia
yo
Nítorí àtiṣe ìrànlọ́wọ́ fún àwọn òbí rẹ̀ àti láti ṣe àtìlẹ́yìn fún ara rẹ̀ lórí ẹ̀kọ́ rẹ̀, Ikeji ma nlo ṣe iṣẹ́ ní àkókò tí kò bá sí ní ẹnu ẹ̀kọ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí onídiúrò láti gba àlejò, aláwòṣe àti òǹkọ̀wé..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2006, ó bẹ̀rẹ̀ sí ní kọ ìwé sínú ìwé ìròyìn orí ẹ̀rọ ayélujára gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ tí ó yàn ní ààyò..
wikipedia
yo
Ní àkókò yí i, ẹ̀rọ ayélujára kò tíì gbìnlé yíká ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ìdí èyí ni ó fi ní láti máa ṣe iṣẹ́ àwọn ìfìwéránṣẹ́ rẹ̀ ní ìdámẹ́wàácafe.Àwọn iṣẹ́ tí Linda Ikeji mọ̀ dájúdájú..
wikipedia
yo
Ikeji bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ìwé kíkọ sí orí ẹ̀rọ ayélujára ní ọdún 2006..
wikipedia
yo
Oríṣiríṣi ètò ni ẹ̀rọ tẹlifóònù Linda Ikeji má a ń gbé jáde lórí afẹ́fẹ́ tí ó fi mọ́ àfihàn ọ̀rọ̀ sísọ, àwọn eré tẹlifísànù lóríṣiríṣi tí ó fi mọ́ àwọn sinimá..
wikipedia
yo
Netiwoki yi ṣe àgbéjáde díẹ̀ nínú àwọn ètò rẹ àti wípé ó tún ra àwọn ònrán tẹ̀léfínù..
wikipedia
yo
Ikeji tún dáwọ́lé ètò agbóhùn sí afẹ́fẹ́ ti orí i ayélujára..
wikipedia
yo
Ibùdó Ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ yí ńṣe iṣẹ́ láti ófìsì àwọn ohun ìgbéròhìnjáde ti Linda Ikeji..
wikipedia
yo
Lára àwọn ètò o rẹ̀ ni wọ́n ń gbé sí afẹ́fẹ́ lórí i tẹlifísíọ̀nù Linda Ikeji.Ikeji tún ṣí pẹpẹ orin kan tí a mọ̀ sí orin Linda Ikeji èyí tí ó ṣe ìfilọ́lẹ̀ ẹ rẹ̀ ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kọkànlá ọdún 2016, ṣùgbọ́n eléyì í kò gbègbè sókè lẹ́hìn oṣù mẹ́ta tí wọ́n ṣe ìfilọ́lẹ̀ ẹ rẹ..
wikipedia
yo
O ṣe ifilọlẹ pẹpẹ nẹtiwọọki àwùjọ kan ti wọn npè ni LindaikejiSocial.com..
wikipedia
yo
Ikeji ń ṣe àgbékalẹ̀ iṣẹ́ àkànṣe kan tí kìí ṣe lórí èrè tí àkòrí rẹ̀ ńjẹ́ "Mo fẹ́ kúkú jẹ́ ti ara à mi; bẹ́ẹ̀kọ́ o ṣeun"
wikipedia
yo
Nínú ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò rẹ̀ pẹ̀lú ilé iṣẹ́ tẹlifísíọ̀nù Hiptv, ó jẹ́ kó di mímọ̀ pé nípasẹ̀ iṣẹ́ àkànṣe yìí ni òun fi máa ńṣe ìrànlọ́wọ́ fún àwọn ọmọ bìnrin kékeré tí ó wà ní ọdún mẹ́rìndínlógún sí ọdún má rùndinlogbon tí wọ́n ní àwọn ìmọ̀ràn ìṣòwò ń lá tí wọ́n sì ṣetán láti bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣiṣẹ́ okòwò..
wikipedia
yo
Ó fún wọn ní àpapọ̀ iye owó tí ó tó mílíọ̀nù mẹ́wàá naira ní ìpele àkọ́kọ́ iṣẹ́ náà.Àwọn oun tí wọ́n fi dá Linda Ikeji mọ̀ ní oṣù kẹjọ ọdún 2021, ni Forbes Afirika ṣe agbátẹrù fún ayẹyẹ àwọn obìnrin Áfíríkà..
wikipedia
yo
Orúkọ ti Linda Ikeji ni ó pọ̀jù lọ tí àwọn ti ń lo ẹ̀rọ ayélujára ti Google ní ilẹ̀ Nàìjíríà ń wá lórí ẹ̀rọ ayélujára yìí..
wikipedia
yo
Ikeji sọ àwọn ìpinnu rẹ̀ fún ọdún tuntun ní ọdún 2020..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2016, Ikeji kólọ sí ilé e rẹ̀ èyí tí ó fi ọ̀pọ̀lọpọ̀ mílíọ̀nù owó naira kọ́..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn ni ó wá sí ibi ayẹyẹ yìí ní pàtàkì àwọn obìnrin ní ilẹ̀ Nàìjíríà.Àwọn àwọn akọ̀ròyìn ń ilé iṣẹ́ BBC fi ọ̀rọ̀ wá Ikeji lẹ́nu wò lórí ètò wọn tí wọn ń pè ní Ìfojúsí lórí Áfíríkà..
wikipedia
yo
Ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò yí wáyé lórí afẹ́fẹ́ ni ó jó karùndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹsan an ọdún 2012..
wikipedia
yo