cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Naa Ashorkor tún ṣe eré pẹ̀lú Yvonne Okoro, JOSÉlyn Dumas àti John Niil .Iṣẹ́ náà Ashorkor, pẹ̀lú òṣèré Chris Attoh olóòtú Vodafone Ghana Music Awards ní ọdún 2016 (Vvmas 2016) tí ó wáyé ní Accra International Conference Centre .. | wikipedia | yo |
Ó tún jẹ́ olóòtú ìdíje Miss Maliaka fún ọdún mẹ́jọ.. | wikipedia | yo |
ó jẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ pẹ̀lú Multimedia Group láti ọdún 2017 títí di ọdún 2020 níbití ó ti ṣe olóòtú èto "Showbiz A-Z" àti "Strong and Sassy" | wikipedia | yo |
ó lọ́ sí ilé iṣẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ Asaaṣe ní ìparí oṣù karùn ọdún 2020 tí ó sì ṣe olóòtú “Between Hours” àti “Just Us” .. | wikipedia | yo |
ní oṣù kẹta ọdún 2021, ó jẹ́ olóòtú fún 3Music Awards.eré tí ó ti kópaìgbésí ayé náà Ashorkor fẹ́ olólùfẹ́ rẹ̀ tipẹ́tipẹ́ Ahuma Cnnyy Adọ̀adji ní ọdún 2014.. | wikipedia | yo |
ní ọjọ́ karùndínlógún oṣù kẹjọ ọdún 2017, ó kéde pé òún bímọ lórí ìtẹ̀jáde ìròyìn.. | wikipedia | yo |
Ó kéde pé òun bímọ ẹlẹ́ẹ̀kejì tí ó tún jẹ́ ọmọkùnrin ní ọjọ́ kínní oṣù keje ọdún 2019.Àwọn ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1988àwọn ènìyàn alààyè.. | wikipedia | yo |
A bí ọ̀gbẹ́ni agbzani Bámidélé George ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù keje ọdún 1973 ní erékùṣù Èkó ní ìpínlẹ̀ Èkó ní Orílẹ̀èdè Nàìjíríà sínú ìdílé Olóyè Alad láti ìlú Togo tó sì fẹ́ ọmọ ìlú Nàìjíríà níyàwó.Olóyè Agbédára fúnrarẹ̀ jẹ́ agbẹ́gilére .Bámidélé George fúnrarẹ̀ yan iṣẹ́ fífi ọ̀dàdára..Bámidélé lọ sí ilé ẹ̀kọ́ alakọbẹrẹ ní ìlú Èkó.. | wikipedia | yo |
Bakana o tesiwaju lati keko fine & Applied Art ni Ile Eko giga Institute of Management & Technology ti Ipinle Enugu o si gboye Higher National diploma ninu ise fifi oda dara.. | wikipedia | yo |
Gbàrà tó gboyèjáde ní ilé ẹ̀kọ́,ńṣe ló gbajúmọ̀ iṣẹ́ ọwọ́ tó yànláàyò nínú ilé àdáni níbi tó ńgbé... | wikipedia | yo |
Finding Hubby jẹ ere fíú ire ifẹ ti a se lati ọwọ Femi Ogunsanwo Awọn akopa ninu ere na ni Kehinde Bankole, Munachi Abi, Ade Laoye, and Omowunmi Dada .. | wikipedia | yo |
O je aṣamudọgba iboju ti ìwègi ti Tunde Leye Ko.Iroko Finding Hubby sọ itan ti Oyin Clegg, Omidan kan ti o jẹ ọmọ ọdun 35 ati awon ọrẹ rẹ bi wọn ṣe sa ipa wọn lati wa sinu wa ni ilu Eko, ni orile-ede Naijiria.Àwọn akopa ninu eré Ade Laoye gẹgẹ bi Oyin Clegg Munachi Abi gẹgẹ bi Gloria Kehinde Bankole gẹgẹ bi Toke Tabeko Aladese gẹgẹ bi Tosan Omowunmi Dada gẹgẹ bi MoRotiti Hassan Efa Iwara gẹgẹ bi Adefemi Omotosho Ael a.. | wikipedia | yo |
Apemiye gege bi Olusoagutan Mama Oyin Samuẹli Asaa gege bi GG Folarin Bankole gẹgẹ bi Rude Guy ni Club Demi Banwo gẹgẹ bi Olumide Sammy Eddy gẹgẹ bi Aminu Oludara Etonton-ng gẹgẹ gẹgẹ bi Iyawo Desmond Charles Etubiebi gẹgẹ bi Ossy Maryann Eziekwe gẹgẹ bi Olusoagutan PA Chris Isibor gẹgẹ bi Ogbeni Kalu Ogunji Tolulope Joy gẹgẹ bi pa to Oyin's Mama ati idasilẹ Finding Hubby Hubby da lori India ṣiṣe ntẹ̀lé ti Tunde Loun ko eyiti o jade laarin osu kerin ati Oṣu Kẹsan ọdun 2012.. | wikipedia | yo |
ó sì jáde ní àwọn sinimá orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ọjọ́ 4 oṣù Kejìlá ọdún 2020.. | wikipedia | yo |
wọ́n gbejade lórí Netflix ní ọjọ́ 9 oṣù keje ọdún 2021.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ ipò 4 lãrín fiimu 10 nípasẹ̀ Olukà fíìmù, Martin CID.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Abẹ́lé jẹ́ ìlànà mímú àwọn ẹranko àti ewéko látinú igbó wásílé láti múwọndára tàbí yíwọn fún lílo àwa ènìyàn bóyá fún ońjẹ,iṣẹ́,aṣọ,òògùn,bàtà àtibẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀lo.ohun ọ̀gbìnláti nkan bíi ẹgbẹ̀rún ọdún mẹ́wàá sẹ́yìn (10,000 years) láwọn ènìyàn tí ń ṣàwárí àwọn ohun ọ̀gbìn onírúùn láàárín àwọn agbègbè bíi Tígírísì,ọgọta ní Mesopotámíà tó gba ìran,Turkey, àti Síríà loni,wọ́n farabalẹ̀ ṣàyẹ̀wò ohun ọ̀gbìn kọ̀ọ̀kan àti ewéko jàjì ṣelé gbín tóàṣà dàáyẹ́ láti mú ońjẹ jáde.Lára àwọn ohun ọ̀gbìn kọ́kọ́ lo ìlànà abẹ́lé fún láwọn orílẹ̀èdè bíi Mesopotámíà, Áfíríkà,Àpà ìwọ àti Ìlà Oòrùn Amẹ́ríkà ní àlìkámà, Ajárí Bálì,Ẹwà Olyìn, Olúkà,ọ̀dùnkún (pò, (tób | wikipedia | yo |
Nígbà Toya wọn fún àwọn ẹranko ńláńlá náà láfiyèsí lati ṣọ̀wọ́n di ẹran ilẹ̀ irúu bíi màálù,Ẹṣin, àti ẹlẹ́pàjì tí n sin àwọn ẹranko yí ní ilẹ̀ bẹ́ẹ̀ ni ìṣesí àti ìwà wọn túbọ̀ ń yàtọ̀ sí tí àwọn babańlá wọn nínú igbó,Fún àpẹẹrẹ látinú ẹ̀yà ìkókó(Wolf Grey)ní ajá tí wà àmọ́ ìwà rẹ̀ ti yàtọ̀ sítí ojúlówó ìkòkò,Bákan náà èdì igbó kìí wúwo jù pọ́ùn méjì lọ, ẹ̀roko ilẹ̀ ma ń wíwò tó pọ́ùn mẹ́tàdínlógún bẹ́ẹ̀ náà Níwọ̀n tún máa ń yé ẹyìn ju ẹ̀dírì lọ gbọ́ gbọ́ gbọ́ àṣeyọrí yìí ṣeéṣe lateri Ìlànà Abẹ́lé abẹ́lé lkókò NAN Óńjẹ pọ̀ síi oríṣiríṣi àìní lowa fún jíjẹ àti jíjẹ ọ̀sìn ilẹ̀ gúnnìyàn iṣẹ́ àgbẹ̀ rọrùn Àpẹẹrẹ tiwọn bá so àjàgà mọ́ akọ màlúù méjì lọ́run fi wọn roko kọjá ibi téèyàn lè ṣeé dé, wọn fi ajá sóde, na ìrìn àjò ró wọn gun ẹṣin tó jìnnà fún ọrọ̀ ajé àti fún àwọn nkan míì.Ọ̀pọ̀ nìyí ló yẹ ó le sọ tán nínú ìlànà abẹ́lé.Àwọn ìtọ́ka sí.. | wikipedia | yo |
The Wedding Party jẹ́ fíìmù àgbéléwò apanilẹ́rìn-ín àti Ajefẹ̀ẹ́ ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó jáde lọ́dún-un 2016 tí Kemi Adetibasi jẹ́ olùdarí fíìmù náà.. | wikipedia | yo |
Àtara àkọ́kọ́ rẹ̀ jáde lọ́jò kejò Oṣù kẹsán-an ọdún 2016 ní Toronto International Film Festival ní Canada ati lọ́̀ kẹrìń Oṣù kọkànlá ọdún kan náà ní Eko Hotel and Suites ni Eko.. | wikipedia | yo |
Àgbégbéjáde fíímù náà wáyé wáyé lódì kẹrìndínlógún Oṣù kejìlá ọdún 2016 tí ó sì jẹ́ fíímù gbé àwọn èèè ń wò jù.àwọn àmọ̀dé ètò rẹ̀ bíi ìni Coker (ìyàwô) W bíi DO ONARẹ̀ru (ọkọ ìyàwó ìyàwó) Mofe Damijo bíi Chief Felix on (baba ọkọ) Ṣódo bíi Mrs.. | wikipedia | yo |
Tinúade Coker (Iya ìyàwó) Iretiola Doyle as Lady Oàánùju Onwuka (Iya ọkọ) Alibaba Akpounji as Gone Bámidélé Coker (Baba ìyàwó)Zainab Balogun as Akande (agbárù ayẹyẹ)na Gugwe as Nonso Onwuka (aburo ọkọ) Somke Iyamah-id Ma as Yemisí dísù (Ore iyawo)Beverly Naya as Rosie (Iyawo ọkọ nígbà kanrí) Down asardre Winston (Ore Iyawo) Zeri Oyetoro as Ayanmale Onun as Sola (Ore ọkọ) Makun as Mce Ece Edun as Wolí (Wolii) Idowu as HarrisonJùmọ̀kẹ́ E as Iya Michael Michael Nzeribe as Luman ( Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Articles with HcardsMichelle Attoh jẹ́ òṣèré orílẹ̀ ède Ghana kan, Olugbohunsan sáfẹ́fẹ́ lórí amóhùnmáwòrán àti Alakoso fún Marketing and Events company.. | wikipedia | yo |
Wọ́n bíi sí orílẹ̀ èdè Ghana sínú ẹbí ògbóǹtarìgì òṣèré orílẹ̀ ède Ghana, Rámà Brew .ise Michelle ni olóòtú today's Woman lórí TV3 .. | wikipedia | yo |
Díẹ̀ nínú àwọn ipá mìíràn tí ó ti kópa nínú iṣẹ́ rẹ̀ ni a ṣe àkójọ sí ìsàlẹ̀.Àwọn ìtọ́kasí àwọn ènìyàn aláàyè.. | wikipedia | yo |
Articles with Hcardsafia Schwarzenegger aka Valentina Nana Agyeiwaa tí a bí ní ọjọ́ kẹrìnlá osù kejì ọdún 1982 sí Kumasi, Ghana jẹ́ oluẹda media ni orílẹ̀ ède Ghana.. | wikipedia | yo |
Ohun ni olóòtú èto Oy FM's morning show yẹ̀wò Krom and utv Ghana's Koko Show.. | wikipedia | yo |
Ohun ni alase Schwar TV lori YouTube ; ati Ọ̀dọ́q Purified water , olóòtú ẹ̀tọ́ The Breakfast show.. | wikipedia | yo |
A yàán gẹ́gẹ́bí aṣojú àwọn aláìya àti bàbá ní Ghana nípasẹ̀ ẹgbẹ́ Association of Children Homes and OrpHánàges ní Ghana. Ó tún jẹ́ olùdásílẹ̀ Leave2live foundation, tí ó jẹ́ ẹgbẹ́ tí ó ran àwọn ènìyàn lọ́wọ́ kúrò níbi ìjà ìkàníkàn abẹ́n.. | wikipedia | yo |
Ó sì jẹ́ olùdásílẹ̀ ti ọ̀wọ́ntáa Street Ministry, ilé iṣẹ́ tí ó ṣàánú àwọn aláìní ní Ghana Afia tún ṣiṣẹ́ fún TV Africa àti káà FM .. | wikipedia | yo |
ó di olókìkí nípasẹ̀ ètò Afia Schwarzenegger TV tíDeloris Frimpong Manso ṣe àgbékalẹ̀ .àwọn Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ni 1985àwọn ènìyàn Alààyè.. | wikipedia | yo |
Articles with Hcardsa bi Beverly Afaglo Baah ni ojo kejìdínlọ́gbọ̀n Oṣù Kaàrún Ọdún 1983.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ òṣèré orílẹ̀ ède Ghana àti olóòtú TV.ÌGBÉSÍ ayé Beverly wá láti agbègbè Volta ní orílẹ̀ ède Ghana.. | wikipedia | yo |
O se igbeyawo pelu Eugene Kwasoro boadu Baah pelu Jiji die won si ni awon ọmọbirin meji.ise Beverly ko eko gegebi onimo nipa bi a se n ṣàtúnṣe ẹwa ni FC Institute of Beauty Therapy, Ghana ó tun je akebo tele ri ni Ghana Institute of Journalism nibi ti o ti ko eko nipa iroyin ati oro to n lo.. | wikipedia | yo |
Yàtọ̀ sí iṣẹ́ eré ṣíṣe, ó jẹ́ Alákoso Éd beauty Salon ní Tema .eré oníṣẹ́ tí sá yan í Love You butreturn of Beyoncé Crime to Christprince's Joseph Againsingle six me on v'segègétorial escapegirls Connectionthe King's Joseph omoluplayboy girls club Club Sugarsecret Burvbout to wẹ́wẹ́ Northern Affair (2014)The Game (2010 film)side Gangaami Eye àti Yíyan Ìtọ́kasí Àwọn Ènìyàn Alààyè Ayun ní 1983.. | wikipedia | yo |
The Smart Money Woman jẹ́ Fíìmù orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Osẹṣe tí ó dá lórí Àràdàdà 2016 tí orúkọ ń jẹ́ Aṣè Ualún.. | wikipedia | yo |
Àtara àkọ́kọ́ rẹ̀ jáde lórí AfricanMagic showcase ní Oṣù kẹsán ní ọdún 2020.. | wikipedia | yo |
A ṣe àwọn fíìmù náà láti ṣe iṣẹ́ ìyàsọ́tọ̀ àti mú ohun tí ó wà nínú ìwé ìdàdàdà náà wá sí ojú ayé.. | wikipedia | yo |
àkokò àfihàn iṣẹ́ yĩ, jáde ní orí AfricanMagic gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ oni'pẹ̀lẹ́ mẹtala.. | wikipedia | yo |
Onse arese ughwu ati Kemi Lala Akindoju lo gbe jade.. | wikipedia | yo |
O ya oSas Ighodárò, Timini Egbuson, Ini Dima-Okojie, Kemi Lala Akindoju ati ọpọlọpọ awọn miiran. ereThe Smart Money Woman jẹ itan awon obinrin marun ati bi wọn ṣe n ṣe iṣakoso inawo ati dukia, itan aramada naa dálé lori eto inawo awọn obinrin ati bi o nse nipa ribiribi lori ọjọ iwaju inawo wọn... | wikipedia | yo |
Ìtàn àràmàdà náà tún sọ̀rọ̀ nípa àwọn ọ̀rẹ́, ìwà nípa àfarawé, àti bí àwọn ipá àwùjọ ṣe ń ṣe àkóso ìnáwó láwọ̀ li ‘jọ́ iwájú.Àwọn òṣèré òsas Ighoró as ZayMI Lala Akindoju as Adesù Kariaye as LaraEbenezer EnoEbenezer as ládùne Edewor as Bangun Egbuson Dakore Bobb Bob stra-Okojie as Tata Ajayi as Síji Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Obi Emelonye lo dárí rẹ̀ àti ìràwọ̀ bí Enyinna Nwigwe tí o ko ipa aṣíwájú gẹ́gẹ́ bí Babangida.. | wikipedia | yo |
ó jẹ́ fíìmù òṣèlú àkọ́kọ́ Nollywood tí ó jẹ́ ọ̀kan gbòógì.Ìdìtẹ̀ Badamasi sọ ìtàn Babangida láti ìpilẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ ní abúlé wúṣhishis ní àríwá ìwọ̀ oòrùn, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà títí di ìgbà tí ó darapọ̀ mọ́ àwọn ọmọ ológun àti àkọ́kọ́ bí Olórí ìjọba Ológun Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
O tun ṣe afihan àwọn iṣẹlẹ pataki ni igbesi ayé Babangida pẹlu akoko Ogun Abẹ́lé Nàìjíríà nibiti Babangida ti ni ipalara nibiti o ti n gbiyanju lati do o la emi ọmọ ologun ẹgbẹ rẹ kan la.. | wikipedia | yo |
Awon ìfipábalẹ ologun ti o tele ati ifagile ti awon idibo Aare June 1993 ni a tun se afihan.Awon akopa Enyinna Nwigwe bi Babangida Charles Injiejie Sani Danja Yakubu Mohammed Okey Bakassi Kalu Ikeagwu Julius Agise Erick Didie2] Fun Badamasi bẹrẹ ni odun 2017.. | wikipedia | yo |
A ṣeto fíìmù náà ní 1980/ìyèdínlọ́gbọ̀n Nàìjíríà àti a ya àwọn aworan rẹ̀ ni Lagos, Minna, Abuja àti fásitì tí Nàìjíríà (UNN), Nsukka.. | wikipedia | yo |
❖ Olùdarí fíìmù náà sọ fún olùfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò Pulse Nigeria kan pé ó gba ọdún mẹ́rin láti fi dá Babangida lójú láti jẹ́ kí ó ṣe fíìmù náà.. | wikipedia | yo |
A fi fíìmù náà sí'ta ní àkọ́kọ́ ní ọjọ́ mọkandinlọgbọn, oṣù Kọkànlá ọdún 2019 ṣùgbọ́n ó dá dúró nítorí “àwọn ènìyàn tí ó lágbára” tí ó lòdì sí káàkiri fíìmù náà.. | wikipedia | yo |
Àwọn ìfiyèsí wà pé Bíjìopic lè jẹ́ iṣúnìyàn láti sọ ìtàn babngídá di funfun bí ifagile ti ìdìbò Ààrẹ June 1993 ṣe jẹ̀bi Babangida.. | wikipedia | yo |
torsten hass (inagijẹ Kim Godàljẹ̀, ti a bi lori 21 Oṣu kọkanla 1970) jẹ olùkàwé ara orilẹ-ede Jemani.. | wikipedia | yo |
Ohun na tun lo je oludari fun ile -ikawe ti ile Yunifasiti kehl am Idr (Baden-Württemberg) lati 1997 de 2014.. | wikipedia | yo |
Eddie Coffie (1959–2015) jẹ́ agbá òsèré ará Ghana, Ààrẹ ẹgbẹ́ àwọn òsèré orílẹ̀ ède Ghana (GAG) àti olùní́n.. | wikipedia | yo |
Ó ṣe ìfihàn nínu ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn eré oníṣe ilẹ̀ Ghana bí "Bob Smith's Diabolo, Dirty Tears Sinking Sands àti a Northern Affair" .Iṣẹ́ ni ọdún 1992, Coffie fara hàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn eré oníse ti ilẹ̀ Ghana bí Bob Smith’s Diabolo, tí ó kó ipa àkọ́kọ́ gẹ́gẹ́bí pásítọ̀-ẹjọ́ tí ó yípadà sí ẹ̀dà àjèjì tí njẹ́ ẹ̀yin tútù tí ó sì ní ìpèníjà ọpọlọ.. | wikipedia | yo |
Ó tẹ̀síwájú láti hàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré oníṣẹ́ bí “Dirty Tears” ní ọdún 1996, Dangerous Game II" àti “The Suspect” ní ọdún 1997.. | wikipedia | yo |
ó sì tún wà nínú àwọn ère oníṣẹ́ “Sinking Sands ní ọdún 2011 àti “A Northern Affair” ní ọdún 2014tí ó ti gba ààmì ẹ̀yẹ.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2014, ó tún wà nínú eré àpapọ̀ Ghana àti Nàìjíríà "My Taxi Soul" pẹ̀lú Martha Aǹhmah, Kalsou Sinare àti Eddie Watson .àwọn òsèré Ghana ní Oṣù Kẹ̀wá ọdún 2014, a yan Coffie gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ àwọn òsèré orílẹ̀ ède Ghana lẹ́yìn tí ó mú ìbò òún nínú mẹ́rinsansan.. | wikipedia | yo |
O jẹ Aare egbe naa ti Olojo fi de ni odun 2015.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ àjọ tó ṣe ìkéde àsà pẹ̀lú tí òsèré àti olósèlú Dzifa Gomashietọ́ Ààrẹ wọn ní ilẹ̀ Ghana.. | wikipedia | yo |
Látàrí ipa tí ó kó gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ GAG, ó ṣiṣẹ́ bí ọmọ ẹgbẹ́ pàtàkì pẹ̀lú Ààrẹ GHAM Kojo Antwi àti Ààrẹ Muce Bíce Odunur láti rí wípé àwọn òsèré mọ̀ nípa ìṣèdúró ní ilẹ̀ Ghana.eré tí ó ti kópa Diabolo (1992) fàtal decision (1993) Who Killed Nancy? (1995) Sarah II (1995) Cand for Hell (1996) Dirty Tears (1996) Dangerous Game II (1997) The Suspect (1997) Burning sàmì 2 (2002) Sinking Sands (2011) Burning sàmì 3 (2012) Burning Desire 4 (2012) The Power of Golítà (2013) a Northern Affair (2014) My Taxi Soul (2014) My Taxi Soul 2 (2014)ìgbésí ayé rẹ̀ Coffie ní ọmọ mẹ́ta; ọmọkùnrin méjì àti ọmọbìnrin kan.. | wikipedia | yo |
ní ọgbọ̀n ọjọ́ Oṣù Kẹ̀wá ọdún 2015, ó kú látàrí ẹ̀jẹ̀ ríru ní ilé- ìwòsàn Ridge .. | wikipedia | yo |
A sin ní ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù Kejìlá ọdún 2015,tí ètò ìsìnkú ìkẹhìn rẹ̀ wáyé ní Azumah Nelson Sports Complex, Kanrgae.. | wikipedia | yo |
pẹ̀lú ojúṣe àti ipa tí ó kó sí iṣẹ́ àti àṣà nínú eré ìtàgé, ìsìnkú ọlọ́lá ní ìjọba orílẹ̀ ède Ghana fi dáa lọ́lá nípasẹ̀ àwọn alákọ́so fún arìnrìn àjo, àṣà àti iṣé ti Alákóso Elizabeth Aâwa-Yaya igbá keji rè re Dzifa Gomashie kópa àti sójú ìjọba níbi ìsìnkú náà.Àwọn ọ̀pọ̀lọpọ̀ akọrin àti òṣèré Jaakan a nii-i Seni Moni Rose (K[K[K) Prince Yalórúkọ (Wàá) (Wàá Augustine Onice (Idiv) Bill Moth Moce Brobbey, Grace Nory, Kojo Susi Saila Sinare, Kaila and bárì. Sidney Nigeria sibi A Adewe Ìtọ́kasí ní Mo Aláìsíl ni 2015 ni 1959 ní 1959.. | wikipedia | yo |
Articles with HcardruRonke Adeola jẹ́ olùdarí eré oníṣe ti orílẹ̀ èdè Nàìjíríà kan, ònkọ̀tàn, oníṣòwò nípa Oge ṣíṣe, olùkọ̀tàn àti olùdásílẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ó gba ẹ̀bùn UNESCO ní bi ayẹyẹ African Film Festivalní ọdún 2019 fún ìwé ìtàn rẹ̀ Àwani .. | wikipedia | yo |
Ó tún jẹ́ òǹkọ̀wé fún ìwé ìròyìn The Guardian àti ThisDay.Iṣẹ́ Adéọlá jẹ́ akẹ́èkó jáde ti ẹ̀ka ìtàn.. | wikipedia | yo |
Ó ti ṣiṣẹ́ tẹ́lẹ̀ ní Ẹ̀ka Ìpolówó Ọjà àti ìbáraẹnisọ̀rọ̀ ni Stanctif IBMC.Ó tún jẹ́ ọ̀kan lára olùdásílẹ̀ ní Red TV saájú kí ó tó lọ sínú ṣíṣe ère oníṣẹ́.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ olùdásílẹ̀ fún ìdásílẹ̀ ìwé ìtàn half of Yellow sun èyítí a ṣe ní ẹ̀dá eré oníṣe.. | wikipedia | yo |
Ó ṣe olùdarí eré oníṣe ìtàn rẹ̀ àkọ́kọ́ awani tí ó jẹ́ kó gba ẹ̀bùn UNESCO ní bi ayẹyẹ African Film Festival ní ọdún 2019 àti ẹ̀bùn àǹfà ní bi ayẹyẹ Impact documentary Awards ní ọdún 2019.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn ọmọ Coààbòbẹ̀rẹ̀ òkọ̀wé ará Nàìjíríààwọn ènìyàn àAlààyè.. | wikipedia | yo |
Erica Ngozi Nokedim tí a bí ní Ọjọ́ ketala Oṣù Kẹta Ọdún 1994 jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, Ariwose, gbajúgbajà aṣat Ori amóhùnmáwòrán àti Alakoso LuXia Hair.O jawe olubori nibi idije Àwọn ọmọbìrin tí ó rewa jùlọ ní orile ede Naijiria ni odun 2014 ti won si yan lati je okan lara akopa ninu gbajugbaja eto "Big Brother Naija (Season 5) (lock Down Edition)" Ayeigbesi ati eko rẹ a bi Erica sinu ebi Eric Ike Nwedim ni Umuahia ni Ipinle Ábíá ni agbegbe ila Oorun Naijiria.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ akéèkó jáde ilé ẹ̀kọ́ Girama Victory Grammar School tí ó sì tẹ̀ síwájú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní ilé ẹ̀kọ́ giga Covenant University nibi ti ó ti keẹ̀kọ́ jáde gẹ́gẹ́ bi alámòójútó owó ṣíṣe, ó sì tún tẹ̀ síwájú láti lọ kẹ́ẹ̀kọ́ ní Met Film School ní London.Iṣẹ́ Ariwoẹ́tun bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ pẹ̀lú Ifẹ̀ tí ó ní sí iṣẹ́ ariwoṣe tí ó sì ni ilé iṣẹ́ rẹ̀ Beluwọ Hair.. | wikipedia | yo |
Iṣẹ ariwoṣe rẹ akọkọ wa lati ọdọ natures Gentle Touch ti o ṣe èròjà ẹya irun ki o to lọ darapò mọ́ ìdíje àwọn ọmọbìrin tí ó rewa jùlọ ni orile ede Naijiria ni bi tí ó ti sojú ìpínlẹ̀ kogi.. | wikipedia | yo |
Ó gba ẹ̀yẹ ẹni tí ó rẹwà jùlọ nínu àwòrán.Iṣẹ́ eré ṣíṣe ní ọdún 2015 lẹ́yìn tí ó jáde ilé ẹ̀kọ́ Met Film School, ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tí ó yàn ìyò tí ó sì kópa ìṣaájú nínú eré oníṣe Secrets and Scandals.. | wikipedia | yo |
Ó ti kópa nínu àwọn eré lórísisi bi Royal Castle àti Being Farou.. | wikipedia | yo |
Erica kó ipa takuntakun ninu eré aláwàdà hire a woman níbi tí orúkọ rẹ̀ ti ń jẹ́ NiFemi.. | wikipedia | yo |
Àwọn àgbà òṣèré ilẹ̀ Nàìjíríà bí Alexx Ekubo, Nancy Isime, Uzor Arukwe ni ó kópa nínu eré náà.. | wikipedia | yo |
Ó tún kópa pàtàkì nínú eré Made in Heaven ti gbajúgbajà òṣèré bí Richard Mofe-Damijo, Toyin Abraham and Ayọ̀ Mákùn kópa níbẹ̀.Àfihàn Ori amóhùnmáwòrán ní ọdún 2020 Erica kópa nínu ètò "Big Brother Naija (Season 5) (lock Down Edition)".. | wikipedia | yo |
Wọ́n ja kúrò laarin wọn ni ọjọ́ kẹfa osu kẹsan odun 2020.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn èyí, wọ́n ṣètò owó u.S dollars ($100k) fún nípasẹ̀ GFundme, tí àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ bàá dá owó tó tó tòótọ́ thousand U.S dollars.. | wikipedia | yo |
Kí o to kuro, Erica tọrọ àforíjì lọ́wọ́ àwọn tí ó ti ṣe wípé ìdààmú ìmọ̀lára tí ohun dojúkọ ló jẹ́ kí ohun wú àwọn ìwà tí ọ̀hún wù sí wọn.Iṣẹ tí ó bu òǹtẹ̀ lu Erica bu òǹtẹ̀ isowọ́pọ̀ pèlú àwọn ilé isé bí Aaron Cosmetics, access Bank PLC and Maltíná.Ère tí ó ti kópa ìgbà diẹ̀ẹ̀rẹ̀ ile Nàìawọn itọkasi “11 Things You Did't Know About BBNija's Erica" | wikipedia | yo |
"Meet BBNija 2020 Housemate Ngozi "Erica" Norodim" | wikipedia | yo |
↑ “I am he here to stay, says Nollywood Actress Erica" | wikipedia | yo |
"Family goals ?! Erica Nwedim had a 'hire a woman' screening party with family" | wikipedia | yo |
↑ “ “Damijo, Ay, Kosoko light up made in heaven" | wikipedia | yo |
"Kidwáyà, Laycon, others talk about Erica's disqualification from show" | wikipedia | yo |
↑ “W*"Tintin fans dey do to ginger Erica, Disqualifiedqualified Big Brother Naija Housemate" | wikipedia | yo |
↑ "Fans Launch $100k Fundra] For Erica BBNija disqualified Housemate" | wikipedia | yo |
Articles with Hcardssjinlẹ̀ Gupta (tí a bí ní ọjọ́ kejìlá Oṣù Karun ọdún 1957) jẹ́ olùdarí aláṣe Sucheta Kriplani Shiksha Niketan (SKSN), ilé-ìwé ibugbe fún àwọn ọmọ tí ó ní ìpèníjà ti ara.. | wikipedia | yo |
A mọ̀ọ́ fún iṣẹ́ rẹ̀ lórí èto amóhùnmáwòrán Sale of the Century àti Angels, bákan pẹ̀lú ipa tí ó kó gẹ́gẹ́ bí ọmọba-bìnrin SusSusta nínú eré.. | wikipedia | yo |
ó tún dá ilé-iṣẹ́ tí ó ṣe iṣelọpọ sílẹ̀.Ìgbésí ayé a bí Gupta ní Kenya ní ọjọ́ kejìlá Oṣù Kakà ọdún 1957, gẹ́gẹ́ bi ọ̀kan nínú àwọn ọmọ márùn fún àwọn òbí rẹ̀ tí ó jẹ́ Indian.. | wikipedia | yo |
Bàbá rẹ̀ jẹ́ olùkọ́, ó sì lọ sí gbogbo ilé-ìwé èyíkè tí ó kọ́.. | wikipedia | yo |
O rìnrìn-àjò Lkokoko bi ọmọdé lati le tele iṣẹ́ olùkó baba rẹ.. | wikipedia | yo |
síbẹ̀síbẹ̀, kò fẹ́ ní nkankan ṣe àti pé ó fẹ́ òmìnira tirẹ̀, ó fi ilé sílẹ̀ ní ọmọ ọdún mẹ́tàdínlógún tí ó sì lo ọdún kan láti kẹ́kọ̀ọ́ ní Germany ṣáájú kí ó tó wá sí England.Ère ṣíṣe àti àwòṣe ní àkọ́kọ́ tí ó n gbé ní Bedford lẹ́yìn tí ó kó kúrò ní United Kingdom ní ọdún 1974, Gupta kọ́kọ́ keekọ́kóo láti di nọ́ọ̀sì.. | wikipedia | yo |
tí ó sì sọ pé ohun ṣe bẹ́ẹ̀ fun yẹ̀yẹ́, ó pinnu láti ṣe ìdánwò Miss Anglia TV, tí ó sì borí, ó sì tún gba òkìkí ní ọdún 1977.. | wikipedia | yo |
Èyí ni ó jẹ́ kí ó di olóòtú fún ètò ITV Gameshow sale of the century pẹ̀lú Nicholas Parsonsfún ọdún kan títí di ọdún 1978, lẹ́yìn èyí ó ṣí ilé ìtajà aṣaralóge tí ìgbàlódé kan tí a pè ní “Pluma” ní Bedford.. | wikipedia | yo |
Gupta wá gbìyànjú iṣẹ́ àwòṣe ṣùgbọ́n ó fi sílẹ̀, nígbà tí ó rí wípé òhun kò lè ṣe é pẹ̀lú iṣẹ́ eré ṣíṣe.. | wikipedia | yo |
Gupta tẹ̀síwájú láti ṣe ìfarahàn nínú Turpin's Progress, Sugalonta, crossroads, Doctor Who (1984's Resurrection of the Daleks), Kim, Tanọrọ Nights.. | wikipedia | yo |
ati Ogasy.Ni ọdun 1981 o kopa ninu ere an Arár Marriage, Ere ITV kan nipa Sikh kan ti o lọ si Midlands ni ọdun 1950s, ati igbeyawo ti a ṣeto fun ati fun ọmọbirin rẹ.. | wikipedia | yo |
Ìtàn náà dá lórí àlàyé láti àwọn ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò pẹ̀lú àwọn Sikh tí ó lé ní àádọ́talénígba.. | wikipedia | yo |
iṣẹ́ rẹ̀ nínú The Far Pavillions engages in suttee, ìṣẹ̀lẹ̀ tí Roy West ṣe àpèjúwe ní Liverpool Echo gẹ́gẹ́ bí "Ọ̀kan nínú àwọn ìfojúsí tí ó ṣe pàtàkì jùlọ nínú àwọn eré ọ̀hún." Ó jẹ́ àlejò lórí Blankety Blank ní ọdún 1987.. | wikipedia | yo |