cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ayodele kúrò nínú ìgbéyàwó náà tí ó sì dojukọ́ ìyá rẹ̀ ..
wikipedia
yo
Eré oníṣe yí parí níbi tí Adenike ti fẹ́ bí ọmọ tí ọkọ rẹ̀ sì lọbawon ní ilé ìwòsàn.Àwọn òṣèré[[ì̀ṣàch de Bankole] gẹ́gẹ́ bi AyodeleDan Gurira géwá gẹ́gẹ́ bi Witakuntakun Ajayi gẹ́gẹ́ bi ma ayo Igbọ̀ngbo gègé gẹ́gẹ́ bi yíÈnìyàn DaCosta gẹ́gẹ́ bi Sade àwọn èyàn nípa eré oníṣe yínínu ọgọ́rún eré yí gba 93% ní Rotten Tomatoes based on 40 Reviews, with an a AÌjàpá of 7.1 Out of 10..
wikipedia
yo
Àwọn èyàn tún tọ́ka eré yí yàtọ̀ àtipé ,George Mother yí ni agbára tí ó sì ṣe àfihàn àwọn òṣèré mẹ́tàèrèẹsẹ̀xèyíkéyìí Ẹ̀wẹ̀ 2013 filmsNigerian filmengìfúntí-language filmsamerican films2013 drama Filmsfilms Set in the United Statesfilms shot in the United Statesfilms Set in BrooklynYorùbá-language filmsNigerian drama Filmsfilms directed by Andrew Dosunmu..
wikipedia
yo
This is a list of Notable pastors in Nàìjíríà, Both Present and PAStoru awon gbajumo pásítọ̀ ni Naijiria Elijah ana oludasile ti Ijo the Gospel Faith Mission International (Gonkomint) Adeboye adari ijo re Remed Christian Church of God (CRC)Paul Adefarasin, Oludasilẹ ati adari Ijo the House on the Rock AkinBERLY, Oludásílẹ̀ ati Adarí Ìjọ The Elevation Church Ashimo Oludásílẹ̀ Oludásílẹ̀ àti Adarí Ìjọ Kings International Christian Centre Joseph Ayọ̀ Tuntun Odásílẹ̀ Tunde Tunde Bakare ati Adarí Ìjọ The Latter Rain Rain. N - N'
wikipedia
yo
Dábalẹ, oludasile Ijo the United Methodist Church in Nigeria (umCN).Jeremiah Mijin Fuf, oludasile ati adari ijo of Christ Mercyland Deliverance Ministry Ibiyeomie, Oludasilẹ ati adari Ijo Salvation Ministriest..
wikipedia
yo
Joshua olùdásílẹ̀ àti adarí ìjọ the synagogue, Church of All Nations - ScoanWilliam F..
wikipedia
yo
ríkúyi (oludasile ati adari ijo Dper Christian life Ministry)Chris Kwatanvwe oludasile ati adari ijo láárurù muọkà oludasile ati adari ijo The Lord's Chosen Charismaticmatic [val Movement.Timothy Oluwole ỌbaDare oludasile ati adari ijo the World Soul winning evangelistic Ministry.Bola Odelékè, oludasile ati adari ijo the Power Pentecostal Church Odukoya, oludasile ati adari ijo.Chris Okotie oludasile ati adari ijo the household of God Church.Gabriel Olutola oludasile ati adari ijo the Apostolic Church Nigeria Emmanuel Omale Odasilẹ ati adari ijo ijo Divine Hand of God Prophetic Ministry.Lawrence Ono jẹ Pásítọ̀ Naijiria ati ALÁBÒÓJÚTÓ gbogbogbòò ti Kings Heritage Church.Ayọ̀ Oritsefor olùdásílẹ̀ ati adari ijo ijo life Bible Samuel Oshoòkú (1909-1985) olùdásílẹ̀ ati adari ijo Celestial Church of Christ C..
wikipedia
yo
C .ChrisChris Oyakh oludasile ati adari Ijo Ijo Christ Embassybishop David Oyedépò oludasile ati adari ijo Winners' Chapel Sulemanman, oludasile ati adari ijo Oayo Fire Ministry, Monkan, Ipinle Edo.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Saidat Adegoke, ti a bi ni ojo kẹrinlelogun, osu Kesan-an (osu SS), odun un 1985 ni ilu Ilorin, Ipinle Kwara, Nigeria, je agbaboolu omo orile-ede Naijiria.Iṣẹ re ni odun 2007, Adegoke bere si ni n gba boolu fun Remo Queens lati ilu re Naijiria, ni ipele Serie A ti orile-ede Italy fun egbe agbaboolu ACF Trento.leyin Serie a akoko ti o kopa fun Trento, o gba boolu wole sinu awon lẹẹmẹta ninu igba merindinlogun ti o kopa..
wikipedia
yo
Ni oṣu kejo (Oṣu Ogun) Ọdun 2008, o kọja si ẹgbẹ agbabọọlu ACF Milan..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó má a fi di ọdún 2011, ó gbá bọ́ọ̀lù wó'le sí'nu àwọn ní'gba ogún-ó-lé-kan nínú igba méjìléláàdọ́ta tí ó kópa.ní ìgbà tí eré bọ́ọ̀lù bẹ̀rẹ̀, ní bíi ọdún 2011 sí 2012, ó kọjá sí ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù FCf Como 2000.Láti ọdún 2010, ó wà nínú ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù orílẹ̀ ède Nàìjíríà ti àwọn obìnrin.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn Alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1985..
wikipedia
yo
Aitán jẹ́ eré oní ṣe tí wọ́n gbé jáde ní orilr Nàìjíríà ní ọdún 2013..
wikipedia
yo
Eré náà gba àmì ẹ̀yẹ eré tó ìlú ní Nollywood ní ọdún ọdún 2013.Àwọn ẹ̀dà ìtàn Femi Adebayo Adebayo Salami Bimbo Akintola Joke Muyiwa Lanre Hassan Iyabo ọkọ Adewale elesho Toyin Adegbòlà Razak Olayiwola TunTun Odunsíàwọn Itoka si..
wikipedia
yo
The Hard case jẹ́ fíìmù orílẹ̀-èdè Britain tí ó jáde ní ọdún 1995..
wikipedia
yo
Guy Ritchie ni ó kọ fíìmù yìí tí ó sì tún darí rẹ̀..
wikipedia
yo
Àwọn akópa fíìmù yìí ni Darren Scer tí ò ṣe the player, Benedick Btes tí ó ṣe player àti Wale Òjó tí ó ṣe Gamlógun..
wikipedia
yo
Fíìmù ogún ìṣẹ́jú yìí gbẹwọ̀n ju fíìmù Ritchie kan tí í ṣe Lock, Stock and Two Smoking Barrels.Àwọn akópa Darren Cè bíi The Player Bene-tes bá bíi a Player Ojo odò bíi The Game Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ọ̀gá Bọlaji jẹ eré oníṣẹ́ kan lati orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ọdún 2018 ti Otan ati oludari jẹ kanode ka ṣu mu..
wikipedia
yo
Ere yi se afihan ikpọnibajade Gold, Omowumi Dada ati Idowu Philips Gẹgẹ bi olu ẹda itan ere onise yi jade ni ojo keje oṣu keje ọdun 2018 ti Awọn irisi awọn eyan nipa ere na nipe oda..
wikipedia
yo
wọ́n ṣe àfihàn ọ̀gá Bolaji ní àwọn ọdún kan bi New York African Film Festival, Nollywood Week Paris, Zimbabwe International Film Festival, RTF Film Festival, Cardiff Film Festival and Zanzibar International Festival..
wikipedia
yo
Oludari ere yi se afihan rẹ lọ́fẹ̀ lori YouTube ni ọdun 2020 fun awọn eyan ti won wa ni ile nigba àtìmọ́lé nipa ajakale coronavirus coronavirus tòótọ́ in the Country.Ọjà oga Bolaji, je akọrin ti ko ko orin mo lati igba ti oti di omo ogoji,bẹni igbesi aye re yi pada lati igba ti o sa la pa de omo obinrin kekere kan ti One Omodun Me je.Awon osere ikpọnbúburú Gold gege bi oga Bolaji Idowu Philips gege bi Mama Bolaji Omowumi Dada gege bi Victoria Gregory ojefua gege bi omo Jasmine fakúnlẹ̀ gege bi ájúa Ronke ojo Officer wòós itọkasiExternal State..
wikipedia
yo
CodeỌ́ Of Silence jẹ́ eré oníṣe ti Bola aduwo ko ti osere olùgbéré-jade Emem Isong gbé jáde ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní 2015..
wikipedia
yo
Royal Art Art Academy àti Nollywood Work fọwọ́sowọ́pọ̀ gbé jáde..
wikipedia
yo
Wọ́n bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú Makida mọ́ka, ẹni tí ó jẹ́ olú-ẹ̀dá ìtàn tí ó kópa gẹ́gẹ́ bí àdánma ..
wikipedia
yo
Ẹrẹ̀ yí dà lé ìtakò ìwà ìfipá báni lò pọ̀ àti ọ̀nà àbáyọ sí ìwà yí pàà pàá jùlọ àwọn tí wọn ti lùgbàdì rẹ̀ rí ni orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.àgbékalẹ̀ eré náààdánmá tí ó jẹ́ olú ẹ̀dá ìtàn tí ó jẹ́ ọmọ akẹ́kọ̀ọ́ ìmọ̀ ìṣègùn, ni olóṣèlú àdúgbò àti àwọn ẹmẹ̀wà rẹ̀ fipá bá ní àṣepọ̀ nígbà tí ó ń bọ̀ láti ilé-ẹ̀kọ́ rẹ̀ wá sílẹ̀..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó dé ilé, ó ṣàlàyé ohun tí ó ṣẹlẹ̀ sí, àmọ́ àwọ̀ obì rẹ̀ gbàá níyànjú láti máṣe sọ ohunkóhun látàrí àìlówó lọ́wọ́ wọn, ẹ̀rù sì tún ń bà wọ́n láti fẹjọ́ sùn fún àwọn agbófinró pẹ̀lú..
wikipedia
yo
Ìfipá-báni lọpọ̀ yí jẹ́ kí àdánma ó ní ìpèníjà oríṣirṣi tí ó sì n ṣàkóbá fún ìgbésí ayé rẹ̀.Àwọn ẹ̀dá ìtàn eré náàMaki mọ́ka gbọ́dọ̀ bí àdánmaPatience Ozokwo Eddọ̀moni Oboliamechi Muonaefi AdJörlolódesmond Elliohudi Faquamna Sod Sojí wọ́n ṣe gbé eré náà jádeàwọn ilé iṣẹ́ àgbèrè-jáde méjì ni wọ́n fọwọ́sowọ́pọ̀ gbé eré náà jáde..
wikipedia
yo
Emem ìsinmi sọ wípé òun gbà láti kópa nínú eré náà nítorí ìlá tí òun ń kọ nípa ìpolongo tako ìwà ìfipá-báni lòpọ̀, nítorí rẹ̀ ni òun sì ṣe ké eré náà jáde pẹ̀lú láti fi dá àwọn ènìyàn lẹ́kọ̀ọ́ pàá pàá jùlọ àwọn tí wọ́n bá lùgbàdì ìwà burúkú náà kí wọ́n lè mọ bí a ṣe ń ké gbàjarè síta nígbà tí wọ́n bá hu irúfẹ́ ìwà bẹ́ẹ̀ sí wọn..
wikipedia
yo
Òun sì gbìyànjú láti bá àwọn ẹ̀dá ìtàn inú eré náà ṣiṣẹ́ pọ̀ nítorí wípé òun ti bá wọn ṣiṣẹ́ rí, wọ́n sì lè ṣe ipa tí wọ́n bá fún wọn dára dára”
wikipedia
yo
Wọ́n fìdí rẹ múlẹ̀ wípé MOP ní ó ń sunkun lẹ́yìn tí ó ti kópa nínu abala tí ó ti dára tàn, èyí èyí fi hàn bí iṣẹ́ náà ṣe mú u lọ́kàn sí.Bí àwọn ènìyàn ṣe gba eré náà gbé eré yé jáde ní ọjọ́ kẹjọ Oṣù Kẹjọ ọdún 2015 ní Silverbird Gvice ní Victoria Island Island ní ìlú Èkó..
wikipedia
yo
Ẹnìkan sọ wípé eré náà le mú kí àwọn tí wọ́n ti farakáṣà ìwà ìfipá bá ní ọlo ó pinu láti má ṣe sọ̀rọ̀ síta mọ́ látàrí ohun tí àwọn ènìyàn yóò ma sọ nípa ìtọ́ka síìtọ́ka sí2015 FilmsNigerian FilmsYorùbá-language Filmsd About Rpe..
wikipedia
yo
ajẹ́jẹ̀ẹ́ze aighewi (tí a bí ní ọjọ́ kọkànlá Oṣù kọkànlá ọdún 1991) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀-ède Nàìjíríà kan tí ó ń gba owó iwájú fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù orílẹ̀-ède Nàìjíríà ..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn tí ó gbá bọ́ọ̀lù nínú ìdíje FIFA World Cup ti ọdún 2011..
wikipedia
yo
ó gbá bọ́ọ̀lù fún ikọ̀ Rivers Angel ní Ìpínlẹ̀ Rivers ní Orílẹ̀-èdè NàìjíríàWòwówọ̀ sí àwọn ènìyàn alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1991..
wikipedia
yo
Ẹgbẹ́ òṣèlú Nigerian Peoples Party (npp) jẹ́ okan pàtàkì nínú àwọn ẹgbẹ̀ẹ́ òṣèlú tí wọ́n ìdíje sípò àṣẹ nígbà ìṣjoba Alágbádá ẹlẹ́kejì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Egbe oselu yi ni o je akojopo egbe oselu meta otooto; awon ni Lagos Progressive, Club 19 ati Nigerian Council of Understanding ti gbogbo won kale si eko Eko..
wikipedia
yo
Lára àwọn tí wọ́n jẹ́ lààmì-laaka inú ẹgbẹ́ òṣèlú náà ní Adéníran Ògúnsànyà, T.O.S..
wikipedia
yo
Benson ati Kola Balogun lati inu ẹgbẹ oṣelu NCNC..
wikipedia
yo
Lóòtọ́, wọ́n dá ẹgbẹ́ òṣèlú yí sílẹ̀ lati díje sípò ìjọba ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Wọ́n dá ẹgbẹ́ òṣèlú yí sílẹ̀ láti fi díje dupò Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ẹgbẹ́ òṣèlú yí ti ní àtìléyìn àwọn íPikọ́ bíi ìmọ̀, Rivers ,Plateau àti Èkó pàá pàá jùlọ àwon Ìpínlẹ̀ apá Ìlà Oòrùn..
wikipedia
yo
Àmọ́, ọ̀gbẹ́ni Waziri fẹ́ di alága ati olùdíje sípò Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú Nigerian Pool's Party..
wikipedia
yo
Gbogbo àwọn abẹnugan inú ẹgbẹ́ òṣèlú náà fà Ààrẹ tẹ̀lé Nnamdi Azikiwe kalẹ̀ lati dije dupò Ààrẹ fún ẹgbẹ́ òṣèlú náà.Wọ́n yan àwọn àwọn ọmọ ẹgbẹ́ wọn sípò òṣèlú bíi Gómìnà, aṣojú nílé ìgbìmọ̀ aṣòfin àti ipò Ààrẹ tí ó jẹ́ ọ̀kan pàtàkì nínú ẹgbẹ́ òṣèlú ní ìpínlẹ̀ ìmọ̀..
wikipedia
yo
Lara awon adibo yan naa ni mbakwe ninu idibo to waye ni orile-ede Naijiria ni odun 1979..
wikipedia
yo
Egbe oselu yi gbe awon igbese to laami-laaka ṣaaju ki idibo gbogbo gbo ọdun 1979 to waye..
wikipedia
yo
Wọ́n já àwọn ọmọ ẹgbẹ́ wọn tí wọ́n tó 254 kúrò nílò adíje dupò òṣèlú, nígbà tí àwọn ọmọ ẹgbẹ́ wọn tí wọ́n jáwé olúborí sí ipò ilẹ̀ Ìgbómìnà aṣòfin àgbà jẹ́ ìdá mẹ́tàdínlógún tí wọ́n sì ní gómìnà mẹ́ta nínú ọmọ ẹgbẹ́ wọn.ìṣèlú ìjọba alágbádá ẹlẹ́kejìni ìṣèlú ìjọba alágbádá ẹlẹ́kejì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ẹgbẹ́ òṣèlú National Party of Nigeria (NPN) náà ní àwọn ọmọ ẹgbẹ́ tó pọ̀ jùlọ nílé Imgbìmọ̀ aṣòfin àgbà, èyí mú ìrẹ́pọ̀pọ̀ wá láàrín àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú ńpp àti NPN tí wọ́n léwájú..
wikipedia
yo
Lára àwọn abẹnugan ẹgbẹ́ òṣèlú ńpp bíi iṣháyà tíu tí ó jẹ́ igbákejì Ààrẹ tí ó ń díje dupò sí ipò Ààrẹ ni wọ́n yàn sípò Mínísítà weak hold on the House of Assembly led to an Alliance Between the Npp and the NPN..
wikipedia
yo
The npp subMITted a few Canther for ministerial Togumentsments to conmate the Alliance..
wikipedia
yo
Npp personalities such as isháyà audu, a vice Presidential candidate of the party, were selected as Minis..
wikipedia
yo
However, the Accord hit the rọ̀cks in 1981, and Adeniran Ògúnsànyà, the chairman of the Party, asked all òpó to resign; many did not heed his call and some transferred to the NPN.Àwọn ìtọ́ka síer Ozbudun, myron weiner; Éjíbítìtitive elections in developing countries, duke university Press, 1987dectct political parties in Nigeria..
wikipedia
yo
Mokálìk jẹ́ fíìmù apanilẹ́rìn-ín ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó jẹ́ Ẹlẹ́dẹ̀ méjì tí a gbé jáde ní ọdún 2019..
wikipedia
yo
Kunle Afolayan ni olùdarí àti ẹni tí ó gbé fíìmù yìí jáde..
wikipedia
yo
Fíìmù náà ṣe àfihàn kò Afolayan tí ó ṣe bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣe tí ó jẹ́ olú ẹ̀dà ìtàn lọ́kùnrin pẹ̀lú Femi Adebayo..
wikipedia
yo
Fíìmù náà jáde ní ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n Oṣù Karun-ún ọdún 2019, ó sì jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà àwọn ará ìlú, kò níṣe ìṣọ̀sí àwọn èèyàn..
wikipedia
yo
Àwọn Netflix ṣe ìtẹ́wọ́gbà fíìmù yìí ní oṣù keje ọdún 2019, wọ́n sì ṣe àfihàn rẹ̀ ní ọjọ́ kìíní oṣù kẹsàn-án, ọdún 2019..
wikipedia
yo
Fíìmù náà ti wà lára àwọn fíìmù abẹ́ "Made in Africa" ní Oṣù Karun-un Ọdún 2020 láti ọwọ́ Netflix tí wọ́n sì máa ṣe àgbéjáde rẹ̀..
wikipedia
yo
A tun yan fiimu naa gege bii fiimu to dara ju lo ni 2019 Durban International Film Festival..
wikipedia
yo
A sì tún ṣe àfihàn fíìmú yìí ní Film Festivals lóríṣiríṣi.Àwọn akópa tòní Afọláyan bíi Ponmile Femi Adebayo bíi Mr..
wikipedia
yo
Ògìdán Wale Akórè bíi bàbá Nepa Charles Okocha bíi Emeka Halimat Nigane bíi Mama gò Alana Inke bíi Borì Fàwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Abọ̀kú jẹ́ fiimu kúkúrú tí wọ́n ṣe ni 2010 nípasẹ̀ Femi Odugbemi àti Olùdarí ní níjì Akannií..
wikipedia
yo
Fíìmù náà gba àmì ẹ̀yẹ fíìmù tó ta yọ ní nu àwọn fíìmù tó kúkúuru jù ní ìgbà gede Zuma Film Festival ní ọdún 2010 àti àmì ẹ̀yẹ fún ẹ̀ṣọ́ tí ó dára jùlọ ní ibi ayẹyẹ ''Africa Movie Academy Awards'' Ele kẹfa irú ẹ̀ tí ó wáyé ní ọjọ́ kẹwa Oṣù Kẹrin ọdún 2010 ní ilé-iṣẹ́ àṣà Gloryland ní agbègbè SGGG, ní ìpínlẹ̀ Gtata, orilede Gaji-ìtọ́ka sí..
wikipedia
yo
The Virgin jẹ iwe ti o tajú ní ọdún 1985 tí Báyọ̀ Adébọ̀wálé jẹ́ akọ̀wé nã.Báyọ̀ adébọ̀wálé..
wikipedia
yo
Ìwé tí wọ́n ṣe àtẹ̀jáde rẹ̀ ní ọdún 1985,sọ nípa wàála tí obìnrin kan dojúkọ ní ìlú rẹ̀ nípa kí ọmú ìkan lára àwọn ọkùnrin mẹ́ta kan tiwọn dá ẹnu ìfẹ́ sí ,tí wọ́n mọ̀ pé ọtíjábalẹ̀ tàbí kí àwọn tú àṣírí ẹ̀ ní alẹ́ ìgbéyàwó rẹ̀..
wikipedia
yo
Scholar Wendy Griswold ṣe àfihàn ìwé yí gẹ́gẹ́ bi "ÌGBÉSÍ AYÉ abúlé"
wikipedia
yo
"Ìwé yí túnṣe àfihàn àṣà àti iṣé ìgbésí ayé àwọn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó sì dàbí akọ̀wé kan ti Óńjẹ Chinua Achebe.àgbékalẹ̀ obìnrin kan tí ó wá láti ilẹ̀ Yorùbá ní abúlé kan, tí òṣì ti fẹ́ òde kan láti abúlé ibòmíràn ..
wikipedia
yo
Béwà ní araáààánú tí ònbo láti ìgboro dá ẹnu ìfẹ́Kò Bena ni ọ̀tún fi owó ra gbogbo ara ẹ̀..
wikipedia
yo
Arábìnrin yí dúró títí di ọjọ́ alẹ́ ìgbẹ́ ìyàwó rẹ̀.Background adébọ̀wálé jẹ́ ẹgbẹ́ “Third Generation tí àwọn akọ̀wé orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọ́n ma ṣe àfihàn àwọn nkan ìgbàlódé tí ófìyàtọ̀sí àwọn akọ̀wé ayé àtijọ́..
wikipedia
yo
Pupọ ninu awọn iṣe Adébọ̀wálé ,oma sonipa awọn ara abule..
wikipedia
yo
adébọ̀wálé ni ìgbàgbọ́ pé àwọn akọ̀wé orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kíwọ́n máṣe àfihàn àwa àti iṣé orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.Àtúnṣe ìwé náà sí eré Oníṣẹ́ Kelani tún ìwé yí ṣe tí òṣì sọdi eré oníṣe tí ó sì darí eré 95-Minute film Version, tí ó aì pe àkọlé rẹ̀ ní Tít The Narrow Path,ti Àwake ní ọjọ́ kẹ́ jí la oṣù karùn ọdún 2012..
wikipedia
yo
eré ṣe àfihàn Sola àṣedekọ, ayọ̀ Badmus àtikGbọ́ọwọ́díà káfìdí ..
wikipedia
yo
múmin wálé ọ̀la àti Frank ẹ̀fẹ̀ Patrick ni wọ́n ṣe àtúnṣe rẹ., tí Abiola Atanda jẹ ẹni tí OF7 wọ́n ní ẹ̀ṣọ́ àti aṣọ..
wikipedia
yo
Eré jẹ́ òtítọ́ sí ìwé náà laye yọ kákún kan kúrò níbẹ̀ bálé ẹ̀jẹ́ pé àfihàn àṣà àti iṣẹ́ wà nínú eré náà.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Àwọn wọ̀nyí ni àtòjọ tọ́jọ́ àwọn oúnjẹ ilẹ̀ Adúláwọ̀, Áfíríkà..
wikipedia
yo
Ilẹ̀ Afirika jẹ́ ilẹ̀ kejì tó tóbi jù ní àgbáyé, pẹ̀lú orísirísi àṣà, ẹ̀yà àti ènìyàn pẹ̀lú oríṣiríṣi oúnjẹ..
wikipedia
yo
Àwọn ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan lọ sìn ní oúnjẹ kọ̀ọ̀kan wọn, àwọn nǹkan tí wọ́n fi ń ṣe é and bí wọ́n ṣe ń ṣe é.Àwọn oúnjẹ ilẹ̀ adúláwọ̀àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Mainframe Films and Television Productions (èyítí a mọ̀ ní Mainframe Studios tàbí Mainframe Films) jẹ́ ilé-iṣẹ́ ìṣelọ́pọ̀ fíìmù tí wọ́n dá sí le ní 1991 nípasẹ̀ òṣèré fíìmù fíìmù ti Nigeria àti olùsẹ̀ fíìmù, Tunde Kelani...
wikipedia
yo
Láti ìgbà ìdásílẹ̀ ní ọdún 1991, ilé-iṣẹ́ iṣelọpọ ti ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn fíìmù olókìkí ti Nàìjíríà..Àwọn iṣẹ́ tó ọtí jádeàwọn itọka sí..
wikipedia
yo
Orílẹ̀ èdè Nàìjíríà jẹ́ ilẹ̀ tí ó kún fún oríṣiríṣi ẹ̀yà tí ó ju 250 pẹ̀lú èdè tí ó tó bí i 500.list of Ethnic groups the following is a non-socgenstive list of Ethnic groups in Nigeria...
wikipedia
yo
Family on fire je ere ti won gbe jade ni odun 2011, ti Tádé Ògìdán dari rẹ̀..
wikipedia
yo
Ohun tí ó ṣe ni wípé, ó fi àpò oògùn olóró kokéènì sínú báàgì ìyá rẹ̀, tí ó ń lò sí ìlú London láti lọ kí àbúrò rẹ̀..
wikipedia
yo
Iya Kunle ja ajá bọ́ lọ́wọ́ àwọn ẹ̀ṣọ́ asọ́bodè ní ìlú London, Kunle fúnra rẹ̀ naa pòfo lati mu òógùn olóró yi kúrò ninu àpamọ́wọ́ ìyá rẹ látàrí bí wọ́n ṣe yí ìrìn-ajo ọkọ òfúrufú tí ó wọ̀ padà láti lọ si UK..
wikipedia
yo
Àmọ́, ìyàwó Fẹ́mi tí ó jẹ́ àbúrò ìyá rẹ̀ Ṣfu-pàdé oògùn olóró náà nígbà tí ó ń tú ẹrù ońjẹ tí ìyá ọmọ rẹ̀ gbé bọ̀ láti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ọmọ ọkùnrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Moyo tí ó sì tún jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ jí oògùn olóró náà gbé níbi tí wọ́n tọ́jú rẹ̀ sí tí ó sì tàá ní owó gọbọi..
wikipedia
yo
Ko pe ko jina, awon ti won gbena fun Kunle bẹrẹ si n dààmú ebi Kunle.Awon ami-eye ti ere naa gbaere yi gba ami-eye ti gbẹ Africa Movie Academy Awards ti o waye ni ojo kejilelogun osu kerin odun 2012 ni Expo Centre ni Eko Hotel &Suites ni Ipinle Eko..
wikipedia
yo
Wọ́n yan eré náà fún àmì-ẹ̀yẹ Best Nigerian Film ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Àwọn àmì-ẹ̀yẹ yí ni wọ́n fún Adesùsù àti State of Violence lọ́tọ̀ọ̀tọ̀.Àwọn ẹ̀dá ìtànSaheed Balógun Aarinzesola fóṣùdosola Sobowalemúra AmosLanre Hassanàwọn ìtọ́ka Ṣínìọnà Films2012 Films2012 Horror FilmsYorùbá-language Filmsfilms Set in Londonfilms Set in Lagosfilms About KáríWàhálàbuctional Familiesfilms About The Fáillegal Drug Tradefilms About Amírànṣáájú2010 Crime Films..
wikipedia
yo
ní ọdún 2017, eré náà gba àmì-ẹ̀yẹ Africa Movie Academy Award for Best Film in an African Language..
wikipedia
yo
Fíìmù náà tún wà lára àwọn eré tí wọ́n gba àmì-ẹ̀yẹ Best African Films of the 21st Century CNN ni ‘’African Voices in 2013tàbi
wikipedia
yo
It was released on DVD in July 2008.Àwọn ìtọ́ka Glms directed by Kunle AfolayanNigerian filmsYorùbá-language films2006 Filmsfilms produced by Kunle Afolayan..
wikipedia
yo
Ìdílé Raro jẹ́ Ìdílé Ọlọ́lá Súnni Mùsùlùmí Nàìjíríà ti ipilẹṣẹ láti Ìpínlẹ̀ Delta..
wikipedia
yo
O dide si olokiki lẹhin ibimọ Dbinrin Raro ti a bi sinu idile onigbagbọ ṣugbọn o yipada si Islam.History itọkasi..
wikipedia
yo
Marcia Virginia Hunt (Ọjọ́ìbí Oṣù Kẹwa 17, 1917) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.Àwọn òṣèré ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Jabubu Nana ní ìwé àkàgbádùn ti Cyprian Ekwen Kò ní ọdún 1961..
wikipedia
yo
Wọ́n kọ́kọ́ gbé ìwé yí jáde ní ọdún 1975, lábẹ́ ilé-iṣẹ́ Heinemann African publisher.Ìwé yí dá lórí iyè-méjì tí ó ń ṣẹlẹ̀e nínú ayé obìrin tí ó jẹ́ olówó Nabi tí ó ti ń dàgbà (jábubu Nana) tí ó jẹ́ olú-ẹ̀dá ìtàn..
wikipedia
yo
Orísirísi àyẹ̀wò ni wọ́n ti fi ìwé yí ṣe pẹ̀lú àwọn iṣẹ́ òǹkọ̀wé Charles Dikúṣamkú, àwọn àyẹ̀wò wọ̀nyí dá le ìgbé ayé àwọn ènìyàn ní inú àwọn ìlú tó ti lajú àti àríwísí nípa ìṣòro àwọn ènìyàn tí ó ń gbé nínú àwọn ìlú wọ̀nyí..
wikipedia
yo
Critics of the work in the 1980s noted that the novel relies heavily on síbínífẹ̀ẹ́ Depictions of women, hampering its depiction of life in Africa.Àwọn ìtọ́ka Si ka síwájú sí 1961 novelsnovels by Cyprian Ekwensino Set in Lago Writers series about proSoṣíọ́lọ́jìdúnàádúrà about proLábẹ́ in Nigeria..
wikipedia
yo
419 Ní ìwé àkàgbádùn ti ọmọ orílẹ̀-èdè Canada tí ó ń jẹ́ Will Ferguson kọ́ ti ilé-iṣẹ́ ìtẹ̀wé Penguin Canada ní ọdún 2012..
wikipedia
yo
Iwe yi ni o gba ami-eye SCotirenk giller Prize ni ọdun 2012.akori iwe yi ni o da lori iwa odaran Agbagba ti Ijoba orile-ede Naijiria n gbogun ti..
wikipedia
yo
Ìwé yí ni ó bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ẹ̀dá ìtàn kan tí ó ń jẹ́ Albert tí ó sì jẹ́ olùkọ́ ní ilẹ̀-ẹ̀kọ́ Calgary..
wikipedia
yo
Albert pàdánù ẹ̀mí rẹ̀ ninu ìjàmbá ọkọ̀ lẹ́yìn tí wọ́n lù ú ní jìbìtì owó tí òun ati ẹbí rẹ̀ sì ti di ẹdun arinlẹ̀..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí ó pàdánù ẹ̀mí rẹ̀, ọmọ rẹ̀ obìrin wá sí ìlú Èkó..
wikipedia
yo