cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ju gbogbo rẹ̀ lọ, ọdún kan lẹ́yìn tí Tinúbú kéde pé kò ní sí ìrànwọ́ orí epo bẹntiróòlù mọ́, ipa wo ni èyí ti ní lórí àwọn ọmọ Nàìjíríà?.
bbc
yo
Ju gbogbo rẹ̀ lọ, ọdún kan lẹ́yìn tí Tinúbú kéde pé kò ní sí ìrànwọ́ orí epo bẹntiróòlù mọ́, ipa wo ni èyí ti ní lórí àwọn ọmọ Nàìjíríà? Orísun àwòrán, Getty Images.
bbc
yo
Ju gbogbo rẹ̀ lọ, ọdún kan lẹ́yìn tí Tinúbú kéde pé kò ní sí ìrànwọ́ orí epo bẹntiróòlù mọ́, ipa wo ni èyí ti ní lórí àwọn ọmọ Nàìjíríà? Orísun àwòrán, Getty Images ìdí tí ìjọba fi ní àwọn yọ ìrànwọ́ orí epo bẹntiróòlù ni pé ọwọ́ tí ìjọba ń ná sì pọ̀ púpọ̀ tó sì jẹ́ wí pé àwọn èèyàn péréte ló ń jẹ ànfàní rẹ̀..
bbc
yo
Ju gbogbo rẹ̀ lọ, ọdún kan lẹ́yìn tí Tinúbú kéde pé kò ní sí ìrànwọ́ orí epo bẹntiróòlù mọ́, ipa wo ni èyí ti ní lórí àwọn ọmọ Nàìjíríà? Orísun àwòrán, Getty Images ìdí tí ìjọba fi ní àwọn yọ ìrànwọ́ orí epo bẹntiróòlù ni pé ọwọ́ tí ìjọba ń ná sì pọ̀ púpọ̀ tó sì jẹ́ wí pé àwọn èèyàn péréte ló ń jẹ ànfàní rẹ̀.
bbc
yo
Wọ́n ní owó tó yẹ kí àwọn máa fi san owó subèrèÓ òhun ni àwọn yóó máa lò láti fi ṣe àwọn ohun amáyédẹrùn tí gbogbo èèyàn yóò jé ànfàní rẹ̀..
bbc
yo
Wọ́n ní owó tó yẹ kí àwọn máa fi san owó subèrè ọ̀hún ni àwọn yóó máa lò láti fi ṣe àwọn ohun amáyédẹrùn tí gbogbo èèyàn yóò jé ànfàní rẹ̀.
bbc
yo
Lọ́pọ̀ ìgbà ni Tinúbú ti sọ pé yíyọ́ sub?”“ ti mú kí àwọn fi ọ̀pọ̀lọpọ̀ owó pamọ́ tí àwọn ń lọ sí àwọn ẹ̀ka mìíràn àti pé yíyọ sub?”“ ti mú kí òun yó inúbu lóko ìparun..
bbc
yo
Orísun àwòrán, Getty Images ìdí tí ìjọba fi ní àwọn yọ ìrànwọ́ orí epo bẹntiróòlù ni pé ọwọ́ tí ìjọba ń ná ṣì pọ̀ púpọ̀ tó sì jẹ́ wí pé àwọn èèyàn péréte ló ń jẹ ànfàní rẹ̀.
bbc
yo
Lọ́pọ̀ ìgbà ni Tinúbú ti sọ pé yíyọ́ sub?”“ ti mú kí àwọn fi ọ̀pọ̀lọpọ̀ owó pamọ́ tí àwọn ń lọ sí àwọn ẹ̀ka mìíràn àti pé yíyọ sub?”“ ti mú kí òun yó inúbu lóko ìparun.
bbc
yo
Ṣùgbọ́n àwọn ọmọ Nàìjíríà ní láti ìgbà tí ìjọba ti yọ ìrànwọ́ orí epo ni ìgbéayé kò ti rọrùn fún àwọn mọ́..
bbc
yo
Ìdí tí ìjọba fi ní àwọn yọ ìrànwọ́ orí epo bẹntiróòlù ni pé owó tí ìjọba ń ná sí pọ̀ púpọ̀ tó sì jẹ́ wí pé àwọn èèyàn péréte ló ń jẹ ànfàní rẹ̀.
bbc
yo
Ṣùgbọ́n àwọn ọmọ Nàìjíríà ní láti ìgbà tí ìjọba ti yọ ìrànwọ́ orí epo ní ìgbéayé kò ti rọrùn fún àwọn mọ́.
bbc
yo
Lára àwọn ará ìlú tó bá BBC News Yorùbá sọ̀rọ̀ ní láti ìgbà tí Ìjọba Tinúbú ti bẹ̀rẹ̀ ní ọdún tó kọjá ni nǹkan kò ti rọrùn fún àwọn mọ́ nítorí gbogbo oúnjẹ ló ti gbówó lórí..
bbc
yo
Lára àwọn ará ìlú tó bá BBC News Yorùbá sọ̀rọ̀ ni lati igbà ti Ìjọba Tinubu ti bẹ̀rẹ̀ ni ọdún tó kọjá ni nǹkan kò ti rọrùn fún àwọn mọ nitori gbogbo oúnjẹ ló ti gbówó lórí.
bbc
yo
Wọ́n ní iye tí àwọn fi ń ra oúnjẹ tì lẹ́kún ní ìlọ́po ọ̀nà látàrí owó epo tó gbówó lórí àti ìjàwálé tó ti bá owó náírà sí dọ́là..
bbc
yo
Lọ́pọ̀ ìgbà ni Tinúbú ti sọ pé yíyọ́ subàìgbàgbọ́ ti mú kí àwọn fi ọ̀pọ̀lọpọ̀ owó pamọ́ tí àwọn ń lọ sí àwọn ẹ̀ka mìíràn àti pé yíyọ́ sub?”“ ti mú kí òun yó inúbu lóko ìparun.
bbc
yo
Wọ́n ní iye tí àwọn fi ń ra oúnjẹ tì lẹ́kún ní ìlọ́po ọ̀nà látàrí owó epo tó gbówó lórí àti ìjàwálé tó ti bá owó náírà sí dọ́là.
bbc
yo
Onímọ̀ nípa ètò orò ajé, Bísí ìyániwúrà ni iṣu kò ṣe é rà lọ́jà mọ nítorí iye tí wọ́n ń ta iṣu ti di nǹkan tí mẹ̀kúnù kò le rà mọ́..
bbc
yo
Onímọ̀ nípa ètò orò ajé, Bísí ìyániwúrà ni iṣu kò ṣe é rà lọ́jà mọ nítorí iye tí wọn n ta iṣu ti di nnkan tí mẹ̀kúnù kò le rà mọ́.
bbc
yo
“Iṣu kò ṣe é rà lọ́jà, àwọn ọlọ́jà ni àwọn èèyàn kò ra iṣu mọ́, iṣu ẹyọkan ni wọ́n ń ta ní ẹgbẹ̀rún mẹta naira báyìí..
bbc
yo
“Iṣu kò ṣe é rà lọ́jà, àwọn ọlọ́jà ni àwọn èèyàn kò ra iṣu mọ́, iṣu ẹyọkan ni wọ́n ń ta ní ẹgbẹ̀rún mẹta naira báyìí.
bbc
yo
“Gàárì ni kí ló ṣubú tẹ ohun ike ọ̀dà gàárì ti di n4,500, bá ṣe ń lọ ńláńlá-in Ọlọrun má jẹ́ kó wò ń6,000.".
bbc
yo
Onímọ̀ nípa ètò orò ajé, Bísí ìyániwúrà ni iṣu kò ṣe é rà lọ́jà mọ nítorí iye tí wọ́n ń ta iṣu ti di nǹkan tí mẹ̀kúnù kò le rà mọ́.
bbc
yo
“Gàárì ni kí ló ṣubú tẹ ohun ike ọ̀dà gàárì ti di n4,500, bá ṣe ń lọ kékeré-in Ọlọrun má jẹ́ kó wò ń6,000.” ÌyàWúrà ni ìjọba kò rí owó kankan fi pamọ́ láti ìgbà tí wọ́n ti yọ ìrànwọ́ orí epo bẹntiróòlù nítorí wọ́n ń lo owó tó pọ̀ ju iye tí tẹ́lẹ̀ lọ láti fi ṣe ìrànwọ́ fún epo..
bbc
yo
“Gàárì ni kí ló ṣubú tẹ ohun ike ọ̀dà gàárì ti di n4,500, bá ṣe ń lọ kékeré-in Ọlọrun má jẹ́ kó wò ń6,000.” ÌyàWúrà ni ìjọba kò rí owó kankan fi pamọ́ láti ìgbà tí wọ́n ti yọ ìrànwọ́ orí epo bẹntiróòlù nítorí wọ́n ń lo owó tó pọ̀ ju iye tí tẹ́lẹ̀ lọ láti fi ṣe ìrànwọ́ fún epo.
bbc
yo
Ó wòye pé ìṣòro tó lágbára ni yíyọ ìrànwọ́ orí epo ń mú bá àwọn ará ìlú àti pé nílò láti sán ṣòkòtò wọn kò lè kí ìdẹ̀kùn lè bá ará ìlú..
bbc
yo
Ó wòye pé ìṣòro tó lágbára ni yíyọ ìrànwọ́ orí epo ń mú bá àwọn ará ìlú àti pé nílò láti sán ṣòkòtò wọn kò lè kí ìdẹ̀kùn lè bá ará ìlú.
bbc
yo
Ó fi kún pé tí ọwọ́ epo àti afẹ́fẹ́ ìdáná kò bá gbówó lórí bí ó ṣe wà báyìí, àwọn ènìyàn máa ní ànfàní láti ṣe iṣẹ́ àmọ́ ipò tí ọrọ̀ ajé Nàìjíríà wà kò ran àwọn ilé iṣẹ́ kéréje lọ́wọ́..
bbc
yo
O fi kun pe tí owó epo àti afẹ́fẹ́ ìdáná kò bá gbówó lórí bí o ṣe wà báyìí, àwọn ènìyàn máa ní ànfàní láti ṣe iṣẹ́ amọ̀ ipò tí ọrọ̀ ajé Nàìjíríà wà kò ran àwọn ilé iṣẹ́ kéréje lọ́wọ́.
bbc
yo
Ó ní ó jọ wí pé ìjọba kò mọ nǹkan tó yẹ kí wọ́n ṣe àmọ́ tí wan kọ̀ láti ṣe nítorí subpó ní nǹkan ṣe pẹ̀lú owó náírà sí dọ́là..
bbc
yo
Ìyàníwúrà ni ìjọba kò rí owó kankan fi pamọ́ láti ìgbà tí wọ́n ti yọ ìrànwọ́ orí epo bẹntiróòlù nítorí wọ́n ń lo owó tó pọ̀ ju iye tí tẹ́lẹ̀ lọ láti fi ṣe ìrànwọ́ fún epo.
bbc
yo
O fi kun pe tí owó epo àti afẹ́fẹ́ ìdáná kò bá gbówó lórí bí o ṣe wà báyìí, àwọn ènìyàn máa ní ànfàní láti ṣe iṣẹ́ àmọ́ ipò tí ọrọ̀ ajé Nàìjíríà wà kò ran àwọn ilé iṣẹ́ kéréje lọ́wọ́.
bbc
yo
Ó ní ó jọ wí pé ìjọba kò mọ nǹkan tó yẹ kí wọ́n ṣe àmọ́ tí wan kọ̀ láti ṣe nítorí subpó ní nǹkan ṣe pẹ̀lú owó náírà sí dọ́là.
bbc
yo
Ìyàníwúrà rọ ìjọba láti pèsè iṣẹ́ fún àwọn èèyàn, kí ètò ọrọ̀ ajé lè gbèrú, tí gbogbo nǹkan yóò sì rọrùn fún àwọn èèyàn..
bbc
yo
Ìyàníwúrà rọ ìjọba láti pèsè iṣẹ́ fún àwọn èèyàn, kí ètò ọrọ̀ ajé lè gbèrú, tí gbogbo nǹkan yóò sì rọrùn fún àwọn èèyàn.
bbc
yo
Orísun àwòrán, others Mínísítà fún ètò Ọ̀gbìn lórílẹ̀èdè Nàìjíríà, Abubakar Kyarí tí ní bí ọ̀wọ́ngógó ṣe gbòde lórí tomato ní àwọn apá ibì kan lórílẹ̀èdè Nàìjíríà, kò ṣẹ̀yìn bí kòkòrò kan ṣe ìkọlù sí àwọn oko tomato.
bbc
yo
Ó sọ èyí lójú òpó ayélujára rẹ̀, tó sì ní pe orúkọ kòkòrò náà tomato Ebola tàbí tomato leaf Miner.
bbc
yo
Kyarí ni gbogbo ọ̀nà ni ìjọba àpapọ̀ ń gbé láti fòpin ìjàmbá tí àwọn kòkòrò ń ṣe sí àwọn ọkọ̀ tomato.
bbc
yo
Púpọ̀ ilẹ̀ ló ti sùn sí lílò tomato ti wọ́n lọ́pọ̀ di pọ̀ èyí tí wọ́n gbé wá láti oko nítorí bí ọ̀wọ́n gógó ṣe gbòde..
bbc
yo
Mínísítà fún ètò ọ̀gbìn lórílẹ̀ Nàìjíríà, Abubakar Kyarí ti ní bi ọ̀wọ́ngógó ṣe gbòde lórí káy ní àwọn apá ibi kan lánìkan Nàìjíríà, ko sẹ́yìn bí kòkòrò kan ṣe ìkọlù sí àwọn oko káká.
bbc
yo
Púpọ̀ ilẹ̀ ló ti sùn sí lílò tomato ti wọn lọ́pọ̀ di pọ̀ èyí tí wọ́n gbé wá láti oko nítorí bí ọ̀wọ́n gógó ṣe gbòde.
bbc
yo
Kyarí ni “ọ̀pọ̀ ọkọ̀ tomato ní àwọn kòkòrò tomato Ebola tàbí tomato leaf Miner yìí ti ṣe ìwà sí..
bbc
yo
Kyarí ni “ọpọlọpọ ọkọ tomato ni àwọn kòkòrò tomato Ebola tabi tomato leaf Miner yìí ti ṣe ìkọlu sí.
bbc
yo
Èyí ló jẹ́ ká a má ri púpọ̀ tomato ní ọjà, tó sì jẹ ohun náà ló ṣokùnfà bi ọ̀wọ́n gógó rẹ̀ ṣe gbòde..
bbc
yo
Kyarí ní gbogbo ọnà ní ìjọba àpapọ̀ ń gbé láti FÒPIN ijamba tí àwọn kòkòrò ń ṣe sí àwọn ọkọ̀ tomato.
bbc
yo
Púpọ̀ ilẹ̀ ló ti sùn sí lílò tomato ti wọn lọ́pọ̀ di pọ̀ èyí tí wọ́n gbé wá láti oko nitori bi ọ̀wọ́n gógó ṣe gbòde.
bbc
yo
Èyí ló jẹ́ ká a má ri púpọ̀ tomato ní ọjà, tó sì jẹ ohun náà ló ṣokùnfà bi ọ̀wọ́n gógó rẹ̀ ṣe gbòde.
bbc
yo
Orísun àwòrán, Getty Images “Ẹ̀ka ètò ọ̀gbìn lórílẹ̀ Nàìjíríà ti ń gbé ìgbésẹ̀ láti kojú ìṣẹ̀lẹ̀ yìí.
bbc
yo
A ti rán àwọn akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ lọ sí ninu àwọn ọkọ̀ tí àwọn kòkòrò yìí ti ṣe ìjàmbá..
bbc
yo
A ti rán àwọn akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ lọ sí ninu àwọn ọkọ̀ tí àwọn kòkòrò yìí ti ṣe ìjàmbá.
bbc
yo
“Láfikún, a yóo ṣe àtìlẹ́yìn ati ìrànlọ́wọ́ fáwọn àgbẹ̀ wa ní kíákíá, kí ìkólọ wọn lè pada..
bbc
yo
“Láfikún, a yóo ṣe àtìlẹ́yìn ati ìrànlọ́wọ́ fáwọn àgbẹ̀ wá ní kíákíá, kí ìkólọ wọn lè pada.
bbc
yo
“A mọ̀ pé èyí ń ṣe àkóbá ńlá fún aráàlú wa ṣùgbọ́n a ṣiṣẹ́ sanra bí gbogbo èyí yóò ṣe di ohun ìgbàgbé, tí ọ̀wọ́n gogò yóò sì di ohun ìgbàgbé.
bbc
yo
“A mọ̀ pé èyí ń ṣe àkóbá ńlá fún aráàlú wa ṣùgbọ́n a ṣiṣẹ́ llori bí gbogbo èyí yóò ṣe di ohun ìgbàgbé, tí ọ̀wọ́n gogò yóò sì di ohun ìgbàgbé ewé ní Mínísítà ní Owó Tõtọ N309bn ní ọwọ́ tí ètò ọ̀gbìn fikún owó ìṣúná Nàìjíríà lórí eré Ọjà tí wọ́n pa wọlé lọ́dún kọjá..
bbc
yo
"Ẹ̀ka ètò ọ̀gbìn lórílẹ̀èdè Nàìjíríà ti ń gbé ìgbésẹ̀ láti kojú ìṣẹ̀lẹ̀ yìí.
bbc
yo
“A mọ̀ pé èyí ń ṣe àkóbá ńlá fún aráàlú wa ṣùgbọ́n a ṣiṣẹ́ llori bí gbogbo èyí yóò ṣe di ohun ìgbàgbé, tí ọ̀wọ́n gogò yóò sì di ohun ìgbàgbé ewé ní Mínísítà ní owó tótọ́ N309bn ní ọwọ́ tí ètò ọ̀gbìn fikún owó ìṣúná Nàìjíríà lórí eré Ọjà tí wọ́n pa wọlé lọ́dún kọjá.
bbc
yo
Ewé ni Mínísítà ní Owó Toto N309bn ní ọwọ́ ti ètò ọ̀gbìn fikún owó ìṣúná Nàìjíríà lórí eré Ọjà tí wọ́n pa wọlé lọ́dún kọjá.
bbc
yo
Orísun àwòrán, Reuters ò ṣeéṣe kí ó ṣàkíyèsí pé ṣokoléètì tí ó fẹ́ràn tí wọ́n ju iye owó tí wọ́n ń tà á tẹ́lẹ̀ lọ.
bbc
yo
JaFar Mohammed, tó ń ta tíì gbígbóná nílùú Kano sọ fún BBC pé iye tí òun ń ta tíì ti pọ̀ ju ti tẹ́lẹ̀ lọ, èyí kò sì ṣẹ̀yìn bí àwọn nǹkan tí òún pò pọ̀ ṣe wọ́n sí.
bbc
yo
Gbogbo èyí kò ṣẹ̀yìn bí ‘Cocoa tó jẹ èròjà tí wọ́n fi ń ṣe tíí ṣe gbówó lórí ní idà 130% láàrin ọdún kan sẹ́yìn.
bbc
yo
Àwọn tó ń gbin kòkó sọ pé ó rí bẹ́ẹ̀ látàrí ọ̀gbẹlẹ̀ àtàwọn àrùn tó ń kọlu oko kòkó..
bbc
yo
Ó ṣeéṣe kí ó ṣàkíyèsí pé ṣokoléètì tí ó fẹ́ràn tí wọ́n ju iye owó tí wọ́n ń tà á tẹ́lẹ̀ lọ.
bbc
yo
Àwọn tó ń gbin kòkó sọ pé ó rí bẹ́ẹ̀ látàrí ọ̀gbẹlẹ̀ àtàwọn àrùn tó ń kọlu ọkọ̀ kòkó.
bbc
yo
Ojú ọjọ́ El Niño tó kọlu àwọn orílẹ̀èdè bíi Ghana àti Ivory Coast, tó jẹ́ orílẹ̀èdè meji tó ní èso kọ́kọ́ jùlọ nílẹ̀ Áfríkà tún ṣàkóbá fún èso ohun..
bbc
yo
Ojú ọjọ́ El Niño tó kọlu àwọn orílẹ̀èdè bíi Ghana àti Ivory Coast, tó jẹ́ orílẹ̀èdè méjì tó ní èso kọ́kọ́ jùlọ nílẹ̀ Áfríkà tún ṣàkóbá fún èso ọ̀hún.
bbc
yo
Jack Scost, tó jẹ́ onímọ̀ nípa iye owó ọjà ní Àjọ Price Futures Group sọ pé “àwọn oníṣòwò ń kọminú lórí bí wọn kò ṣe ní lè rí èrè tó tó jẹ lọ́dún yìí látàrí bí ojú ọjọ́ ṣe rí pẹ̀lú wàhálà tí El Niño ń dá sílẹ̀.".
bbc
yo
Jack Scost, tó jẹ́ onímọ̀ nípa iye owó ọjà ní Àjọ Price Futures Group sọ pé “Àwọn oníṣòwò ń kọminú lórí bí wọn kò ṣe ní lè rí èrè tó tó jẹ lọ́dún yìí látàrí bí ojú ọjọ́ ṣe rí pẹ̀lú wàhálà tí El Niño ń dá sílẹ̀.” Ní ti Mohammed tó ń ta tíì, ó ní “Inú mi kò dùn bí ọjà náà ṣe ń gbówó lórí àmọ́ kò sí nǹkan tí mo lè ṣe sí.".
bbc
yo
Jack Scost, tó jẹ́ onímọ̀ nípa iye owó ọjà ní Àjọ Price Futures Group sọ pé “Àwọn oníṣòwò ń kọminú lórí bí wọn kò ṣe ní lè rí èrè tó tó jẹ lọ́dún yìí látàrí bí ojú ọjọ́ ṣe rí pẹ̀lú wàhálà tí El Niño ń dá sílẹ̀.” Ní ti Mohammed tó ń ta tíì, ó ní “Inú mi kò dùn bí ọjà náà ṣe ń gbówó lórí àmọ́ kò sí nǹkan tí mo lè ṣe sí.” Mohammed, tó máa ń pa nǹkan bíi ẹgbẹ̀rún mẹ́ta náírà lóòjọ́ tẹ́lẹ̀ ni òun gbọ́dọ̀ fi kún owó ọjà òun kí tí òun kò bá fẹ́ kógbá wọlé..
bbc
yo
Jack Scost, tó jẹ́ onímọ̀ nípa iye owó ọjà ní Àjọ Price Futures Group sọ pé “Àwọn oníṣòwò ń kọminú lórí bí wọn kò ṣe ní lè rí èrè tó tó jẹ lọ́dún yìí látàrí bí ojú ọjọ́ ṣe rí pẹ̀lú wàhálà tí El Niño ń dá sílẹ̀.” Ní ti Mohammed tó ń ta tíì, ó ní “Inú mi kò dùn bí ọjà náà ṣe ń gbówó lórí àmọ́ kò sí nǹkan tí mo lè ṣe sí.” Mohammed, tó máa ń pa nǹkan bíi ẹgbẹ̀rún mẹ́ta náírà lóòjọ́ tẹ́lẹ̀ ni òun gbọ́dọ̀ fi kún owó ọjà òun kí tí òun kò bá fẹ́ kógbá wọlé.
bbc
yo
Ìwọ oòrùn ilẹ̀ Afrika ni wọ́n ti ń rí ìdá 70% koko tí wọ́n fi ń tìí àti ṣokoléètì lágbàùn..
bbc
yo
Ìwọ oòrùn ilẹ̀ Afrika ni wọ́n ti ń rí ìdá 70% koko tí wọ́n fi ń tìí àti ṣokoléètì lágbà.
bbc
yo
Ní ti Mohammed tó ń ta tíí, ó ní “Inú mi kò dùn bí ọjà náà ṣe ń gbówó lórí àmọ́ kò sí nǹkan tí mo lè ṣe sí.” Mohammed, tó máa ń pa nǹkan bíi ẹgbẹrun mẹta naira lóòjọ́ tẹ́lẹ̀ ni òun gbọdọ̀ fi kún owó ọjà òun kí tí òun kò bá fẹ́ kógbá wọlé.
bbc
yo
orisun aworan, Reuters lati ọdun meji sẹyìn ni iye koko ti won n ri ka ni Ghana ati Ivory Coast ti n dinku..
bbc
yo
Mohammed, tó máa ń pa nǹkan bíi ẹgbẹ̀rún mẹta naira lóòjọ́ tẹ́lẹ̀ ní òun gbọdọ̀ fi kún owó ọjà òun kí tí òun kò bá fẹ́ kógbá wọlé.
bbc
yo
Orísun àwòrán, Reuters láti ọdún méjì sẹ́yìn ní iye kókó tí wọ́n ń rí ká ní Ghana àti Ivory Coast ti ń dínkù.
bbc
yo
Àjọ tó ń bojútó ọ̀rọ̀ kòkó ní Ghana, Cocobod sọ pé àrùn kan tó máa ń mú kí kókó wú ti pa ilé ọkọ tí iye rẹ̀ tó ẹ̀ka 500,000 rẹ̀..
bbc
yo
Àjọ tó ń bojútó ọ̀rọ̀ kókó ní Ghana, Cocobọ̀ sọ pé àrùn kan tó máa ń mú kí kókó wú ti pa ilé ọkọ tí iye rẹ̀ tó ẹ̀ka 500,000 rẹ̀.
bbc
yo
Cocobod ni arun naa maa n pa Kkook bẹẹ lo tun maa ba ile ọkọ jẹ..
bbc
yo
Cocobo ni arun naa maa n pa Kkook bẹẹ lo tun maa ba ile ọkọ jẹ.
bbc
yo
Ojú ọjọ́ tó móoru ju bó ṣe yẹ lọ náà tún pa kún ìṣòro ọ̀hún..
bbc
yo
Láti ọdún méjì sẹ́yìn ní iye kókó tí wọ́n ń rí ká ní Ghana àti Ivory Coast tí ń dínkù.
bbc
yo
Ojú ọjọ́ tó móoru ju bó ṣe yẹ lọ náà tún pa kún ìṣòro ọ̀hún.
bbc
yo
Ní Ivory Coast, tọ́ọ̀ kọkọ tí iye rẹ̀ tó 2.6m ni wọ́n rí níbẹ̀ láàrin ọdún 2022 sí 2023 àmọ́ àmì tí wá pé ó ṣeéṣe kí wọ́n má rí tó iye náà lọ́dún 2023 sí 2024..
bbc
yo
Ní Ivory Coast, tọ́ọ̀nù kọ́kọ́ ti iye rẹ̀ tó 2.6m ni wọ́n rí níbẹ̀ láàrin ọdún 2022 sí 2023 àmọ́ àmì ti wà pé ó ṣeéṣe kí wọ́n má rí tó iye náà lọ́dún 2023 sí 2024.
bbc
yo
Orísun àwòrán, Reuters ́ bó tilẹ̀ jẹ́ pé iye tó wu oníkálukú ló ń ta kókó rẹ̀ ní Nàìjíríà, Cocobod ló ń ṣàkóso iye iye owó ní Ghana..
bbc
yo
Orísun àwòrán, Reuters ́ bó tilẹ̀ jẹ́ pé iye tó wu oníkálukú ló ń ta kókó rẹ̀ ní Nàìjíríà, Cocobod ló ń ṣakoso Iye Iye Kò ní Ghana.
bbc
yo
Ni Ghana ati Ivory Coast, ijoba lo maa ń pinnu iye owó tí wọ́n gbọdọ̀ ta kókó..
bbc
yo
Orísun àwòrán, Reuters ́ bó tilẹ̀ jẹ́ pé iye tó wu oníkálukú ló ń ta kókó rẹ̀ ní Nàìjíríà, Cocobod ló ń ṣàkóso iye iye kókó ní Ghana.
bbc
yo
Ni Ghana ati Ivory Coast, ijoba ló maa ń pinnu iye owó tí wọ́n gbọdọ̀ ta kókó.
bbc
yo
Lọ́dún tó kọjá, ìjọba Ghana kéde pé àwọn tó ń ta kòkó jèrè ti iye rẹ̀ tó ìdá àádọ́ta ṣùgbọ́n inú àwọn àgbẹ̀ tó ń gbin kòkó náà kò dùn sí iye tó wọlé sí àpò wọn..
bbc
yo
Lọ́dún tó kọjá, ìjọba Ghana kéde pé àwọn tó ń ta kòkó jèrè ti iye rẹ̀ tó ìdá àádọ́ta ṣùgbọ́n inú àwọn àgbẹ̀ tó ń gbin kòkó náà kò dùn sí iye tó wọlé sí àpò wọn.
bbc
yo
Àwọn àgbẹ̀ náà ni ìyà tí wọn ń jẹ lórí kókó kò tó iye owó tí àwọn fúnra wọn ń rí lórí rẹ̀..
bbc
yo
Bo tilẹ̀ jẹ́ pé iye tó wu oníkálukú ló ń ta kókó rẹ̀ ní Nàìjíríà, Cocobod ló ń ṣàkóso iye owó kòkó ní Ghana.
bbc
yo
Àwọn àgbẹ̀ náà ni ìyà tí wọn ń jẹ lórí kókó kò tó iye owó tí àwọn fúnra wọn ń rí lórí rẹ̀.
bbc
yo
Ẹ̀wẹ̀, àwọn tí ọ̀rọ̀ kan bíi Àjọ Tó Ń Rí Sí Ọ̀rọ̀ kọ́kọ́ lagbaye, ICO, tí ke sí àwọn iléeṣẹ́ tó ń pọ̀ ṣokoléètì àti ìjọba pé kí wọ́n kówó tó pọ̀ sórí kòkó kí nǹkan lè rọrùn fún àwọn àgbẹ̀ tó ń gbin kòkó náà àtàwọn aráàlú tó ń rà tíì àti ṣokoléètì àtàwọn nǹkan míì tó ń jáde láti ara kòkó..
bbc
yo
Ẹ̀wẹ̀, àwọn tí ọ̀rọ̀ kan bíi Àjọ Tó Ń Rí sí Ọ̀rọ̀ kọ́kọ́ lagbaye, ICO, tí ke sí àwọn iléeṣẹ́ tó ń pọ̀ ṣokoléètì àti ìjọba pé kí wọ́n kówó tó pọ̀ sórí kòkó kí nǹkan lè rọrùn fún àwọn àgbẹ̀ tó ń gbin kòkó náà àtàwọn aráàlú tó ń rà tíì àti ṣokoléètì àtàwọn nǹkan míì tó ń jáde láti ara kòkó.
bbc
yo
Orísun àwòrán, Reuters lọ́sẹ̀ tó kọjá, iléeṣẹ́ Soapry, tó ń ṣe ìpara nílẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì sọ fún àwọn oníbárà rẹ̀ pé ọ̀wọ́ngógó kọ́kọ́ ń ní ìpalára lórí ọwọ́ òun..
bbc
yo
Orísun àwòrán, Reuters lọ́sẹ̀ tó kọjá, iléeṣẹ́ soapry, tó ń ṣe ìpara nílẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì sọ fún àwọn oníbárà rẹ̀ pé ọ̀wọ́ngógó kọ́kọ́ ń ní ìpalára lórí ọwọ́ òun.
bbc
yo
Oludasilẹ iléeṣẹ́ naa, Andy Knowles sọ fún BBC pe oun ti fi owó ti iléeṣẹ́ naa ni si ìpamọ́ ra kókó tán látàrí bi kókó ṣe wọn tó..
bbc
yo
Oludasilẹ iléeṣẹ́ naa, Andy Knowles sọ fún BBC pe oun ti fi owó ti iléeṣẹ́ naa ni si ìpamọ́ ra kókó tán látàrí bi kókó ṣe wọn tó.
bbc
yo