cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ní ọdún 1621 ó kọjá sí Paris, ní ibi tí ó ti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Nicolas Poussìn níbi ìṣẹ́ṣó fún Palais du Luxembourg lábẹ́ ìtọ́sọ́nà Nicolas Duchesne, tí ó fẹ́ ọmọ rẹ̀ married..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bihoukenken ti sọọ́ di mímọ̀, inú bí Duchesne sí Champaigne nítorí wípé ó gbajúmọ̀ Júù lọ ní Court, èyí ni ó jẹ́ kí Champaigne padà sí Brussels láti lọ máa gbé pẹ̀lú ẹ̀gbọ́n rẹ̀..
wikipedia
yo
Ìgbà tí ó gbọ́ ìròyìn nípa ikú Duchesne ni ó sẹ̀sẹ̀ padà lọ fẹ́ ọmọ rẹ̀..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ikú olùdáàbòbò Duchesne, Champaigne ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ìyá olórí, Marie de Medicis, tí ó ti wà lára àwọn tí ó ṣe ààfin Luxembourg lẹ̀ṣọ́.Ó ya àwọn àwòrán oríṣiríṣi fún Notre Dame Cathedral ní Paris, ní bíi ọdún 1638 sẹ́yìn..
wikipedia
yo
Wọ́n yàn-án ní ayàwòrán àkọ́kọ́ fún olórí tí ó sì gba ẹgbẹ̀rún àti ìgbà pọ̀nhùn fún iṣẹ́ rẹ̀..
wikipedia
yo
Ó tún ṣe ẹ̀ṣọ́ fún ilé ìjọsìn CarMelite ti Paradisebourg Saint-Jacques, tí ó jẹ́ ìkan lára àwọn ilé ìjọsìn tí ìyá olorì yàn láàyò.Wọ́n ba ibẹ̀ jẹ́ nígbà àyípadà Faransé ṣùgbọ́n àwọn àwòrán wa tí wọ́n tọ́jú sí àwọn ilé ọ̀nà tí ó wà lára àwọn ẹ̀ṣọ́ àkọ́kọ́ (èyí tí wọ́n ṣe ní pẹpẹ wà ní Dijon, àjínde Lásárù wà ní Grenoble ti ìgbàbo ìbálé sí wa ní is Louvre..
wikipedia
yo
O tún ṣiṣẹ́ fún Cardinal Richelieu, tí ó ṣe èèè Palais Cardinal, tí ó jẹ́ òfurufú Sorbonne àti àwọn ilé míràn..
wikipedia
yo
Champaigne ni oníṣẹ́ ọnà tí wọ́n gbà láàyè lodará ya àwòrán Richelieu tí wọ́n fi sàmì, tí ó ṣe ní ìgbà mọ́lẹ̀..
wikipedia
yo
Ó wà lára àwọn olùdásílẹ̀ Académie de peinture et de sculpture ní ọdún 1648..
wikipedia
yo
Nígbà ayé rẹ̀ (láti 1640 síwájú si), ó ṣalábápàdé Jansenism..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ìyanu tí ó gbé ọmọ rẹ̀ tí kò lè rìn dìde ní Port-Royal, ó ya àwòrán ẹ̀yẹ yìí Ex-tọ́ De 1662, tí ó wà ní Louvre, tí wọ́n fi ṣàpèjúwe ọmọ ayàwòrán yìí pẹ̀lú ìyá àkin Agnes Arnauld.Iṣẹ́ rẹ̀ Champaigne ya àwọn àwòrán tó pọ̀, tí ó ní ṣe pẹ̀lú iṣẹ́ ẹ̀sìn..
wikipedia
yo
Rubens too sono ni ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀, àwọn iṣẹ́ rẹ̀ sì dára..
wikipedia
yo
Philippe de Champaigne jẹ́ ayàwòrán tí iṣẹ́ rẹ̀ yàtọ̀, a dúpé fún àwọn awọ alábara tí ó maa ń tayo ní iṣẹ́ rẹ̀.ilé àwòrán rẹàwọn Ìtọ́kasí àwọn Ojoalaisi ni 1674..
wikipedia
yo
Àfin Beaumont , tí wọ́n Henry I kọ́ sí gúúsù ọnà ìrińrin Oxford ní ọdún Paja gẹ́gẹ́ bí àfin Ọba kí ó lè sunmo ibi tí Ọba ti ń gbé ní Woodsji (sí ó jẹ́ ara ìfin Blenheim). Àwọn ìtọ́kasí àji kukuru..
wikipedia
yo
Jonathan Raymond "Jon" Polito (29 Oṣù Kejìlá 1950 – 1 Oṣù Kẹ̀sán 2016) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.Àwọn ìtọ́kasíàwọn òṣèré fíú ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Andrew Clement "Andy" Serkis (April 10, 1964) jẹ́ òṣèré ara Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan.Ìtọ́kasíàwọn òṣèré fíú ará Britani..
wikipedia
yo
Ebute Metta jẹ́ èèè ìlú Èkó, ní ìpínlẹ̀ Èkó, orílẹ̀ èdè Nàíjíríà.orúkọ Ebute Metta jẹ́ ọ̀rọ̀ Yorùbá fún ibi tí ó jẹ́ etí òkun mẹ́ta..
wikipedia
yo
Ebute túmọ̀ sí etí òkun tí mẹ́ta sì túmọ̀ sí mẹ́taitan wọn mọ́ Ebute Metta sí ìṣíṣètò ìsó àti àwọn aṣeni..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ibìkan ní ìlú Èkó tí ó ti wà tipẹ́,ọpọlọpọ àwọn ilé tí ó wà níbẹ̀ ni wọ́n ti kọ́ ní ìgbà ìletò àkọ́kọ́, tí wọ́n sì kọ́ àwọn ilé tí ó wà níbẹ̀ bí èyí tí ó wà ní orílẹ̀ èdè Brazil..
wikipedia
yo
Awon ayika re ni ile ijosin St Jude ati ile iwe African Salem School ati ile ijosin Salvation Army..
wikipedia
yo
Gbogàn Lisabi jásí Ayika Okobaba ati Osa.Awon ile ti o wa nibe Ebute Metta ni awon ile ti o lókìkí ati olúIle Iṣẹ Nigerian Railway Corporation, ilé ìwé ranse, ilé ìjọsìn St Paul's Catholic, Oja Oyingbo Oyingbo, ibùdó Oko, Foucos Secondary School (ilé ìwé ti Minisita fún ètò ẹ̀kọ́ tẹ́lẹ̀ kọ́), St..
wikipedia
yo
Saviour's School, Junior strides Academy, Ajayi Memorial Hospital, Ebute Metta Health Centre, ati àwọn ilé ìtajà oriṣiriṣi..
wikipedia
yo
O tun je ona kan ti o ja si awon agbegbe kan bi eniyan ba n wa oko lati Iddo.Awon itọkasiawon ìjápọ century awon ibi ti o ni se pelu ebute Mettacom Category with local link same as on WikiDatani Wikimedia Commonsilu Eko..
wikipedia
yo
Baptist Boys’ High School jẹ́ ilé ìwé girama ní Abeokuta, ìpínlẹ̀ Ògùn, Gúúsù-Iwọ̀ oòrùn Nàíjíríà..
wikipedia
yo
Ó ní àwọn akẹ́kọ ẹgbẹ̀rún lé ọgọ́rún ní ọdún 2011 sí 2012..
wikipedia
yo
Àwọn akẹ́kọ yìí dínkù dé ìdajì lati 2155 ní ọdún 1998 sí 1999, látàrí láti ri wípé kí òun èlò fún ẹ̀kọ́ lè tó wọn..
wikipedia
yo
BBHS wà ní ibùdó rẹ̀ ní Oke-Saje.ìtàn Baptist Boys’ High School di dídásílẹ̀ nípasẹ̀ àṣrò àwọn ará Amẹ́ríkà ti Gúúsù Baptist tí wọ́n beere iṣẹ́ ní ìlú Abeokuta ní ọjọ́ karún Oṣù kejo, ọdún 1850 àti Didé alufaa Thomas Jefferson Bowen tí ó jẹ́ ajíyìnrere àkọ́kọ́, àti oníwònu ìsìnsùn, ará Amẹ́ríkà ti Gúúsù Baptist sí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, ṣètò ilé ìwé, ọ̀wo iwosan, ilé ìwé fún àwọn olùkọ́ fún àwọn ilé fún àwọn tí àwọn ti o fẹ́ nípa BÍBÉLÌ..
wikipedia
yo
Irinajo Baptist ti ilẹ̀ Nàìjíríà jẹ́ ẹ̀ka ti orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà tí ó dá ilé ìwé alábẹ̀rẹ̀ mẹ́ta sílẹ̀ sí Ago-Owu, Ago-Ijaye àti Oke-Saje lẹ́yìn tí àwọn akẹ́kọ ti ilé ìwé alábẹ̀rẹ̀ ti Owu gbooro sí 150, wọ́n sọ fún ÀLÙFÁÀ Samuel Ésí ní ó dá ilé ìwé tí ó ga jù jùka jùka sílẹ̀..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1916 Pinnock ṣe àwárí ibùdó, òkè Egún , tí ó sì ra ilẹ̀ náà..
wikipedia
yo
Kíkọ́ ilé ìwé yìí kò yára rárá nítorí Ogun Àgbáyé tí ó jẹ́ kí gbogbo nkan ìkọ́lé gbówó lórí..
wikipedia
yo
Bákan Nan, ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ọdún 1922 Pinnock ríi dájú wípé ibùgbé olórí ilé ẹ̀kọ́ náà di kíkọ́, tí ó sì tún jẹ́ ilẹ̀ àwọn ajíyìnrere ti Abeokuta; yàrá ìkàwé márun, ilé ìjọsìn àti yàrá fún àwọn ọkùnrin.Ní ọdún 1922 Pinnock sá àwọn akẹ́kọ tí ó ti ní ìmọ̀ díẹ̀ láti àgọ́-òwú, àgọ́-Ìjàyè àti Òkè-ṣàjẹ́, tí wọ́n sì jẹ́ akẹ́kọ àkọ́kọ́ ní gírámà yìí..
wikipedia
yo
Ó sí Baptist Boys’ High School ní Ọjọ́ kẹtàlélógún Oṣù kínín ọdún 1923, pẹ̀lú àwọn akẹ́kọ 75 àti OLÙKỌ́ mẹ́rin (pẹ̀lú ìyàwó rẹ̀, MaDora Pinnock)..
wikipedia
yo
Àjò pàtàkì tí ó soro níbẹ̀ ní ọ̀jọ̀jọ̀gbọ́n Professor Nathaniel Oyerinde, tí ó jẹ́ olùkọ ní ilé ẹ̀kọ́ ìwòjínjú Baptista, Ògbómọ̀sọ́, tí ó sì jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n Baptist àkọ́kọ́ ti orílẹ̀ èdè Nàíjíríà.Wọ́n dá Baptist Boys’ High School sílẹ̀, tí ó sì wà bẹ́ẹ̀, gẹ́gẹ́ bí ilé ìwé fún àwọn ọkùnrin, bí wípé wọ́n kọ́ àwọn obìrin mọ́ àwọn obìrin ní ọdún 1969, nígbà 1969, nígbà tí àwọn àjọ tí àwọn ní ìwé.. School..
wikipedia
yo
Ile iwe yii gbooro si 400 ni osu kejila odun 1946, ati si Didara ni bi odun 2011 si 2012.egbe akekojade BBH Old Boys Association ni eka si UK/Ireland, USA/Canada, Abeokuta, Ibadan, Ijebu Ode, and Abuja.Awon akekojade ti won gbajumo Obafemi Awolowo Olusegun Obasanjo Bola Ajibola Gbenga Daniel Funsho Kupọlọ Moshood Abiola Dimeji Bankole Thomas Adeoye Mév Adegboyega Dosunmu Amororo II II Oyedo Oyed Olawale AB Kayode Soyinka Onaolapo Soleye Sunday Abibi Aesove Aremu Gbadebo III Alani Orikonwe sinu Iamika si School The School Book 1923- 2017-S, Abeokuta, Abeokuta.
wikipedia
yo
Jonathan Michael "Jon" Lovitz (July 21, 1957) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.Àwọn ìtọ́kasíàwọn òṣèré fíú ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Akarigbo ti Remo tàbí Olorun Remo jẹ́ oyè ọba tí ọba Yorùbá ti ilú Sagamu máa ń jẹ..
wikipedia
yo
Ìlú yìí àti àwọn agbègbè rẹ̀ jẹ́ ara ìlú tí wọ́n máa ń pè ní Ijẹ̀bú.Ị̣̣̀̀̀ rẹ̀ ỌBA ÌLÚ Remo ti wà tipẹ́ láti ìgbátí tí omo Oba Oyo tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ óbàǹtà ti dá ìlú Ijebu sílẹ̀ àti ìgbà tí ọmọ ọba Àkarìgbò ti wá sí ìwọ̀oòrùn ìlú náà ní bíi Orundún mẹ́rìndínlógún sẹ́yìn..
wikipedia
yo
Wọ́n maa ń fi orúkọ yìí dá àwọn ọba Sagamu, lọ́lá ní orúkọ ọmọ ọba àkọ́kọ́.orí ìpò àwọn Ọba Àkari kókó wà ní agbègbè Remo gbẹ́lẹ̀ offin, ìlú méjì tí ó wà ní ìwọ̀ oòrùn ibi tí iṣẹ́ náà wà sísí lá..
wikipedia
yo
Látàrí ọ̀wọ́ ẹrú ní Dahomey àti ogun tí ó wáyé láàrín àwọn olóyè Abeokuta àti àwọn Ọba Dahomey, tí ó fàá kí àwọn Yorùbá kúrò ní Abeokuta àti ìwọ̀ oòrùn Dahomey lọ sí karigbo tí ó sì jẹ́ kí o wọ́n wà ní ìṣàkóso àwọn Ọba Adékari..
wikipedia
yo
Ohun tí ó tún fàá ni ṣíṣubú òde Ọ̀yọ́ tí ó ṣẹlẹ̀ dé gúúsù Ìjẹ̀bú àti ogun ddd tí ó ṣẹlẹ̀ ní ilẹ̀ Hausa, tí Usman Dan fodio tí ó jẹ́ Fúlàní ṣe adarí rẹ̀..
wikipedia
yo
Láti lè dojú ìjà kọ́ ìhàlẹ̀ yìí, àwọn olórí ẹgbẹ́ kọ̀kan sì dá Sagamu sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bi ibi tí àwọn ènìyàn ti ogun bá lé kúrò ní gúúsù àti ìwọ̀ oòrùn lè sá pamo sí.fin karí ti ìlú Remoàwọn ìtọ́kasíàwọn ogun..
wikipedia
yo
Hannah Idowu Didelo Awolowo (àbí Adelana; Ojo karùndínlọ Oṣù kọkànlá ọdún 1915 – Ojọ́ ọkàndínlógún oṣù kẹsán ọdún 2015), tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí HIDTA, jẹ́ ọmọ bí ọmọ bí ìlú kékeré kan tí wọ́n ń pè ní Ikenne ní ìpínlẹ̀ Ogun ní orílẹ̀ èdè Nàíjíríà..
wikipedia
yo
ó fẹ́ olóṣèlú tí a mọ̀ sí Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ láti ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 1937 di ìgbà tí olóṣèlú náà fi kú ní ọdún 1987..
wikipedia
yo
O maa n pèé ní "Òkúta iyebiye tí kò lẹ́gbẹ̀".ìgbésíayé jẹ́ ògbónta oníṣòwò àti olóṣèlú..
wikipedia
yo
O ko ipa ribiribi ninu òṣèlú ìwọ̀ oòrùn orílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O duro ti oko rẹ nigba ajọṣepọ ẹgbẹ oṣelu NCNC ati AG, ti wọn pe ni United Progressive Grand Alliance (Ugaga), nigba ti o n ṣẹ̀wọ̀n lọ́wọ́.Èrò wọn ni wipe ki o dije fun ibo naa ti o ba si wọle ki o si jẹ ki ọkọ rẹ bọ sori alefa latari ibo tiwantiwa..
wikipedia
yo
Kí ó lè di Ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, ó ń tẹ̀lé ọkọ rẹ̀ kákáká orílẹ̀ èdè Nàìjíríà láti rọ àwọn ènìyàn kí wọn ó dìbò fún..
wikipedia
yo
Ó tún jẹ́ adarí àwọn obìrin ẹgbẹ́ òṣèlú náà tí ó sì máa ń wà ní gbogbo ìpàdé ẹgbẹ́ náà..
wikipedia
yo
Gewe bi oniṣowo, o jẹ obinrin akọkọ ti o maa jẹ alabapin ọja fun Nigerian Tobacco company (ntc) ni ọdun 1957..
wikipedia
yo
Ohun ni ó máa kọ́kọ́ kó aṣọ lẹ́èsì àti àwọn aṣọ míràn bẹ́ẹ̀ wọ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ní ọjọ́ ọ̀kàndínlógún oṣù kẹsàn ọdún 2015, Ó jẹ́ Ọlọ́run nipé lẹ́yìn tí ó lo ọdún ọ̀kandínlọ́gọ́rùn láyé, oṣù méjì kí ó ṣe ọjọ́ ìbí ọgọ́rùn ọdún..
wikipedia
yo
Wọ́n sìnkú rẹ̀ sí ẹgbẹ́ ọkọ rẹ̀ ní ìkẹ́nnẹ́ ní ọjọ́ karùn oṣù kẹsàn ọdún 2015.Àwọn ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1915àwọn oníṣòwò ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Amy Meredith Poọmú (September 16, 1971) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.Àwọn ìtọ́kasíàwọn òṣèré QFI ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
High Court of Lagos State jẹ́ ilé ẹjọ́ tó ga jùlọ ní ìpínlẹ̀ Èkó..
wikipedia
yo
O ni ẹka meji, ikan wa ni Erekusu Eko ti ekeji si wa ni Ikeja.Oloye Oloogbe Conrad Idowu Taylor ni o kọkọ jẹ adajọ agba ni High Court of Lagos State ni ọdun 1967, ki o to fẹyìntì.Awon itọkasiÀyọkà kukuru..
wikipedia
yo
Jackie Chan (ti won bi ni ojo keje osu kerin odun 1954) je osere ati olóòtú sinimá àgbéléwò, ọ̀kọrin ọmọ orílẹ̀ èdè China...
wikipedia
yo
Sinimá rẹ̀ máa ń dá lé ìjà afipá àti gídígbò jà.Àwọn ìtọ́kasí àyọkà kúkúrú..
wikipedia
yo
Lagos City Hall tí a mọ̀ sí gbọ̀gán ìlú Èkó di dídásílẹ̀ ní ọdún 1900..
wikipedia
yo
Ó kalẹ̀ sí agbègbè àwọn ará Brazil, ní àárín ẹ̀kọ́ níbi tí ọrọ̀ ajé ti ń lọ..
wikipedia
yo
Nicholas Hospital, Lagos àti Cathedral of the Holy Cross, Lagos..
wikipedia
yo
Gbọ̀ngàn Ìlú yìí jẹ́ olú ilé ìjọba ìbílẹ̀ tí àwọn agbègbè míràn sì wà fún ìṣètò ìjọbaìjọba ìbílẹ̀ ti ìletò Èkó lẹ́yìn tí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà gba òmìnira..
wikipedia
yo
Gbọ̀ngàn ìlú yìí ní àkókò ìjọba ìbílẹ̀ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí ó sì jẹ́ olú ilé ìjọba ìbílẹ̀ gúúsù èkó níbi tí ètò ìjọba ti bẹ̀rẹ̀ ní Nàìjíríà láti ọdún 1900..
wikipedia
yo
Gbọ̀ngán yìí jẹ́ ohun ìtàn, òṣèlú, tí ó sì ní ṣe pẹ̀lú àṣà ìlú Èkó.otun lè ka pápá isere OnikanFreedom ParkQueen Amina Staolóyè National MuseumLagos Trade Fair ComplexTafawa Balewa SquareTeslim Balogun StadiumBar Beach, Lagoskuta RepublicMKO Abiola Statue Abéèrèment ParkNational Temple Ìtọ́kasí àyọkà kukuru..
wikipedia
yo
King's College, Lagos jẹ́ ilé ẹ̀kọ́ sẹ́kọ́ndírì ní ìpínlẹ̀ Èkó..
wikipedia
yo
Wọ́n dáa mó\ ní ọjọ́ ogún oṣù kẹsán ọdún 1909 pẹ̀lú àwọn akẹ́kọ mẹ́wá ní Erékùṣù Èkó, lẹ́gbẹ́ Tafawa Balewa Square..
wikipedia
yo
Ìlé ẹ̀kọ́ yìí máa ń gba ọkùnrin nìkan, bíótilẹ̀ jẹ́ wípé àwọn obìnrin díẹ̀díẹ̀ wà lára wọn (A Level) àwọn akẹ́kọ HSC kí wọ́n tó dá Queen's College Lagos , sílẹ̀ tí a mọ̀ sí kọ́lẹ́jì obìrin..
wikipedia
yo
Báyìí, àwọn akẹ́kọ náà maa ń bá àwọn ẹlẹgbẹ́ wọn ṣe ìdánwò West African School-Leaving Certificate àti National Examinations Council.Ìtàn nípa rẹ̀ ní ọdún 1908, Alákòso ètò ẹ̀kọ́ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, Henry rawlingson Carr gba Gómìnà Walter Egerton ní ìyànjú lórí ètò ẹ̀kọ́ ní Ìpínlẹ̀ Èkó..
wikipedia
yo
Ìyànjú Carr àti àwọn ìmọ̀ràn rẹ̀ ní ó jẹ́ kí wọ́n dá King's College sílẹ̀..
wikipedia
yo
Carr jẹ́ kí àwọn London Board of education rí wípé dídá ilé ìwé yìí sílẹ̀ máa mú ìtẹ̀síwájú bá ètò wọn nípa ẹ̀kọ́ ní àwùjọ..
wikipedia
yo
Fun idi eyi, awon Olùkọ̀wé kan maa n pe Henry Carr ni "atukọ̀ King's College".Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Badagry Division jẹ́ ilé jẹ́ ilé ìgbìmọ̀ fún ìṣètò ìpínlẹ̀ Èkó, Nàíjíríàjáde nípa rẹ̀ Badagry Division jẹyọ nínú ìtàn ìbáṣepọ̀ láàrín orílẹ̀ èdè Nàíjíríà àti Yuràrà, tí ó sì dì tí ọjà tí wọ́n ti ṣwọ́ ẹrú ẹrú wà nígbà tí àwọn Bìrìkókó kó wọn lẹ́rú..
wikipedia
yo
Ó tún jẹ́ ibi tí àwọn ẹlẹ́ṣin igbagbọ ti kọ́kọ́ kéde ìyìn rere ní ọdún 1842 ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Eyi di àkọ́sórí fun àwọ̀le Ceph.Awon ijoba ibile o ni ijoba ibile merin ojo Amuwo-Odofin Jèhófàrọ̀mí-Ifelodun Badagryawọn ibugbe awon ibugbe ni ibile Badagry pin so ona meji..
wikipedia
yo
Àmọ́ àpẹrẹ tó dára làwọn méjì nítorípé àwọn ẹ̀yà méjẽjì ngbé papọ̀ lálãfíà láìsí wàhálà..
wikipedia
yo
Steven Frederic Seagal jẹ oṣere ati atọkun sinima agbelewo ọmọ orilẹ ede Amẹrika.Awon itọkasi àyọkà kukuruawon osere ara Amerika..
wikipedia
yo
Khary Payton (May 16, 1972) jẹ́ òṣèré ara Amẹ́ríkà.Àwọn ìtọ́kasíàwọn òṣèré fíú ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Candido Joao Da Rocha ( 1860 - 1959) jẹ́ oníṣòwò ọmọ orílẹ̀ èdè Nàíjírìa, tí ó jẹ́ onílẹ̀, ayánilówó tí ó n Water House tó wà ní àdúgbò von kàkàwa , Lagos Island, Lagos, tí ó tún ní ilé ìtura Bonanza tí ó wà ní ìlú Èkó.Da Rocha jẹ́ ọmọ bíbí Iléṣà, tí wọ́n bí sí inú ẹbí Joao Esan Da Rocha, tí ó jẹ́ ẹrù tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀; bàbá rẹ̀ jẹ́ ọmọ ọdún mẹwa nígbà tí wọ́n kóo lẹ́rú ní ọdún 1840 tí wọ́n sì bí Candido sí Bahia agbègbè kan ní orílẹ̀ èdè Brazil.Àwọn ìtọ́kasíàwọn Ọjọ́ìbí ní 1860àwọn Ọjọ́aláìsí ní 1959àwọn oníṣòwò ará Nàìjíríàka kúkúrú..
wikipedia
yo
Nguyễn Chanh Thi (Ọjọ kẹtàlélódún Oṣù kejì ọdún 1923 - Ọjọ́ kẹtàlédún Oṣù kẹfà ọdún 2007) jẹ́ ológun ilẹ̀ Vitenam (AR)..
wikipedia
yo
Wọ́n mọ̀ọ́ sí àwọn ipa tí ó kó nínú fífipá gba ìjọba ní bí 1960 tí ó sì wà lára àwọn ológun tí ó ṣe ìjọba Gúúsù Vietnam láti ọdún 1964 sí 1966, tí ó sì jẹ́ wípé nígbà tí ọ̀gá ológun òfurufú ti ilé Vietnam àti alákóso tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Nguyễn ìwẹọdún Ký borí rẹ̀, ó koja sí Amẹ́ríkà. Wọ́n mọ̀ọ́ sí àwọn ìwà bìbìkí tí kò ń fẹ́ gba ìmọ̀ lọ́wọ́ u.S, àwọn olórí ẹgbẹ́ ní Amẹ́ríkà sì fi owó sí bí wo ṣe yọ ṣe yọ lọ..
wikipedia
yo
Thi darapọ̀ mọ́ ọmọ ogun ilẹ̀ Faransé nígbà tí ó pé ọmọ ọdún mẹ́tàdínlógún, tí àwọn Japan sì kọ́O Mògún lọ nígbà tí wọ́n dojú ogun kọ French Indochina nígbà ogun àgbáyé kejì..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ọpọlọpọ oṣù, ó na pápá bora. Ó padà darapọ̀ mọ́ ológun Vietnam ti Faransé tí state of Vietnam ń ṣaláìbọ fún, èyí, ní oṣù kẹwa ọdún 1955, di Arvn ati Republic of Vietnam (Gúúsù Vietnam)..
wikipedia
yo
Ó ja fún alákóso ìgbà yẹn tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ NGO HHH Diệm nígbà 1955 Battle for Saigon..
wikipedia
yo
Thi mú orí Diệm wú tí ó sì jẹ́ kí ó maa pèé ní “ọmọ mi” tí ó sì sọ ọ́ di apàṣẹ Airborne Brigade.Ní ọdún 1960, Thi síwájú ìfipá gba ìjọba lọ́wọ́ Diệm, ń sọ wípé ológun dásí òṣèlú. Àwọn ọwòlé yìí borí ṣùgbọ́n Thi kò fi taratara fẹ́ borí ogun náà tí ó sì fa ìdí́ fún ìfipá gba ìjọba náà, lẹ́yìn tí Diệm fi ẹbí bí ìnira láti ṣe àfi fi àkókò ṣòso sí àwọn ènìyàn tiè lè gbàá sílẹ̀..
wikipedia
yo
Thi sá kúrò ní ìlú lọ sí Cambodia, ṣùgbọ́n, ó padàwà lẹ́yìn tí wọ́n yọ Diệm tí wọ́n sì paá ní oṣù kọkànlá ọdún 1963..
wikipedia
yo
Ó di igbákejì apàṣẹ tí í Corps lábẹ́ Nguyen Khanh, tí ó sì bá ọ̀gá rẹ̀ gbàjọba lẹ́yìn oṣù mẹ́ta..
wikipedia
yo
Thi di apàṣẹ 1st Division, kí ó tó di alákóso I Corps lẹ́yìn ìgbà díẹ̀ lọ́dún náà.Awon ìtọ́kasíàwọn Ọjọ́ìbí ní 1923àwọn Ojoaláìsí ní 2007àyọkà kukuru..
wikipedia
yo
Teresa Teng (January 29, 1953 – May 8, 1995), àwọn gbajúmọ̀ Taiwanese singer ni àṣíá, ó ní àsíá gbajúmọ̀ àti àsíá Pop Music Ayaba..
wikipedia
yo
Ó kọrin Chinese Songs, Japanese Songs, Indonesian Songs, 21 Songs,ẹsẹ̀ àwọn orin ati English Songs..
wikipedia
yo
Ní 1974, ó àtẹ̀jáde rẹ̀ àkọ́kọ́ Japanese album ní Japan.ní Japan, ó jẹ́ kan olókìkí singer..
wikipedia
yo
Ní 1983, ó ṣe ní Caesars Palace ní Las Vegas àti kí ó ṣe àìbalẹ̀ ọkàn..
wikipedia
yo
Ní afikun, ó ní ó ní díẹ̀ ẹ́ síì ju 500 tí a tí yàn Ayljr..
wikipedia
yo
rẹ̀ Songs ni ó wà gidigidi gbajúmọ̀ ní Asia, bí Taiwan, Hong Kong, China, Japan, South Korea, North Korea, Malaysia, Indonesia, Singapore, Thailand àti àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn, ó ní ó ní díẹ̀ ẹ̀ síi ju 1 bilionu egeb..
wikipedia
yo
Bákan, on 8 May 1995, ó kú ní Chiang Mai, Thailand, àti àwọn fa ti ikú wa ikọ̀ọdún
wikipedia
yo
Ẹ̀ May 28, 1995, Àwọn Taiwan ìjọba tí ó wáyé á Ṣáyín ìsìnkú fún u láti má ńṣerántí àwọn tí ó tóbi Taiwanẹsẹ̀ singer...
wikipedia
yo
Eko Hotels and Suites jẹ́ ilé ìtura onípele marún ní ìlú Èkó.Àwọn ilé ounjẹ mẹ́jọ ọ̀tọ̀ àti ilé ọti mẹ́jọ ní ó wà ní ilé ìtura yìí.ìtàn nípa rẹ̀ wọ́n dá sílẹ̀ ní ọdún 1977 bí ẹ̀kọ́ Gday Bari àti wọ́n sì kọ́ sí Victoria Island, ó sì jẹ́ ilé ìtura tó tóbi jùlọ ní ìlú Èkó..
wikipedia
yo
Wọ́n yí orúkọ rẹ̀ sí Le Meridien Eko Hotel and Suites, Eko..
wikipedia
yo
L'Hotel Eko Le Meridien jẹ́ ara ilé iṣẹ́ Chagoury Group.KÍKỌ rẹ̀ ilé ìtura yìí ní yàrá bíi 825 sí ilé alájà mẹ́rin tí ó tóbi, wọ́n kùú ní funfun, òkun wa ní iwájú rẹ̀ àti etí ọsà Kùrámọ̀..
wikipedia
yo
Ibi tí wọ́n kọ́ sí yìí máa ń jẹ́ kí àwọn ènìyàn ní áààárín láti wọ òkun àti àyíká tí ó jẹ́ kí wọ́n máa n pèé níEnvironment of Aquàti SBójúnìkan..
wikipedia
yo
Awon ohun igbalode ti o wa ni ile itura yii maa n je ki awon eniyan láánfàní si awon ile ise ńláńlá.Awon ayeye Eko Hotels and Suites ni aye ti o tobi fun ayeye ti o si tobi julo ni orile ede Naijiria..
wikipedia
yo
Awọn ayẹyẹ ti wọn ti ṣe nibẹ ni ajọdun orin, Isagbejade ere, iṣafihan iṣẹ ọna, ayẹyẹ igbeyawo ati ayẹyẹ bii Africa Magic Viewers Choice Awards, Africa Movie Academy Awards, AGRIXXPO, ati oriṣiriṣi iṣafihan ọlọ́dọọdún bi Lagos Photo Festival..
wikipedia
yo