cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Imú jẹ́ ẹ̀yà ara ti ènìyàn àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹranko fi ń gbòrun..
wikipedia
yo
Gbígbọ́ òórùn wúlò fún ìgbádùn(.“run lọ́fíńdà tàbí oúnjẹ tó ní òórùn tó dùn lè mú inú ènìyàn tàbí ẹranko dùn) àti ìkìlọ̀ ewu(bí apẹ̀rẹ̀; gbígbọ́ òórùn Gaaṣi tí òun jó, gbígbọ́ òórùn ẹranko apanirun)..
wikipedia
yo
Ihò inú imú jẹ́ ọ̀nà tí èémí ńgbà wọlé sínú ènìyàn àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹranko, ó sì tún jẹ́ ọ̀nà tí èémí ngba jáde.ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Martin Patterson hing (ọjọ́ìbí oṣù July 19, 1924 – January 3, 2009) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.Àwọn òṣèré ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Michael Gough (Ọjọ́ìbí Oṣù November 23, 1916 – March 17, 2011) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.Àwọn òṣèré ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Richard Schiff (Ọjọ́ìbí Oṣù May 27, 1955) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.Àwọn òṣèré ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Douglas Carl "Doug" ẸgelBart (Ọjọ́ìbí Oṣù January 30, 1925 – July 2, 2013) jẹ́ Inventor ará Amẹ́ríkà...
wikipedia
yo
Richard Burton Matheson (20 February 1926 – 23 June 2013) jẹ́ Olùkọ̀wé ará Amẹ́ríkà.Àwọn Olùkọ̀wé ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Ninu tẹnis, Marion Bartoli ati Andy Murray gba ife-ẹ̀yẹ ìdíje Wibledon 2013.07..
wikipedia
yo
Philip Jaisohn and Philip Jason(Oṣù Kínní 7 1864 – Oṣù Kínní 5 1951) je Dokita ara Korea guusu to kopa ninu Olatima ati oniroyin..
wikipedia
yo
Oruko rẹ̀ ni Korea N Sese E-Piljìnkasí àwọn ara Korea gúúsù..
wikipedia
yo
yùn Chi-họ(yunci Yin Zzz Inz , 26 December 1864 - 9 December 1945) jẹ́ olóṣèlú àti amòye ará Korea gúúsù tó kópa nínú ìgbòmìnira..
wikipedia
yo
A tún mọ̀ sí Jwáong.Ìtọ́kasí àwọn amòyeàwọn ara Korea gúúsù..
wikipedia
yo
Pran Krishan síkand (ọjọ́ìbí 12 Oṣù Kejì 1920 – 12 Oṣù Keje 2013) jẹ́ òṣèré ará India.Àwọn òṣèré ará India..
wikipedia
yo
Shinto ( Shinto) — Japan Esin.Ìtọ́kasí ẹ̀sìnJapanShinto..
wikipedia
yo
Park Heon-Young(Bghe Po Xan Yong , 28 May 1900 – 5 December 1956) jẹ́ olóṣèlú, oníròyìn àti Amẹ́tàsti ará Korea gúúsù tó kópa nínú gbígbà Ìlọway ilẹ̀ Korea..
wikipedia
yo
Oruko alaje re ni yijeong tabi Yhunhunjiji awon ara Korea guusuawon amòyeiseìtẹ́lọ́rùn..
wikipedia
yo
Park Jung-yang(bagàkọsílẹ̀yang pọ́ ZHong Yang , 3 May 1872 - 23 April 1959) nínú Dókítàlọ́mọ and ìṣèlú, Libedlism àwọn Amòye gba Korea gúúsù..
wikipedia
yo
Governor of GyongSanz-do, Jeolllanam-do, Pyongannam-do, CHunÉjíbítì-nam, Hwang-e-do, CHung-ony-do- Province..
wikipedia
yo
He was a conscientious pro-Japanese idìdker and ìṣèlú..
wikipedia
yo
Oruko alaje re ni HaEA tabi Ilso.jàka Park Jung-yang (Korea) * Park Jung-yang (Korea) * Park Jung-yang (Korea) àwọn ará Korea Gúúsù amòye..
wikipedia
yo
(born January 17, 1982), Nicknamed FLAsh or D-Wade, jẹ́ agbábọ́ọ̀lù alápẹ̀rẹ̀ ará Amẹ́ríkà.Ìtọ́kasí agbábọ́ọ̀lù alápẹ̀rẹ̀ ara Américo tó gba ohun wúrà wúrà látinú fún-èdè Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Lebron Raykáwọn James (; bíi ọjọ́ ọgbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 1984), ìnagijẹ rẹ̀ n jẹ́ "King James", jẹ́ agbábọ́ọ̀lù alápẹ̀rẹ̀ ọmọ orílẹ̀ ède AMẸ́RÍKÀ.Àwọn Ìtọ́kasíÀyọkà kukuruàwọn agbábọ́ọ̀lù alápẹ̀rẹ̀ ara AmerikàáWọ́n tó gba èso Wúrà Wúrà fún orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Juwan António Howard (ojoibi February 7, 1973) je agba boolu-alapere ara Amerika.Ìtọ́kasí agbaboolu alapere ara Amerika..
wikipedia
yo
Michael Lloyd Miller (ọjọ́ìbí February 19, 1980) jẹ́ agbá bọ́ọ̀lù alápẹ̀rẹ̀ ará Amẹ́ríkà.Ìtọ́kasí agbábọ́ọ̀lù alápẹ̀rẹ̀ ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
jẹ́ agbábọ́ọ̀lù alakan ará Amẹ́ríkà.Ìtọ́kasíàwọn agbábọ́ọ̀lù alapẹrẹ ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
AlMario Vernard "Mario" Chalmers (Ọjọ́ìbí May 19, 1986) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù alápẹ̀rẹ̀ ara Amẹ́ríkà.Ìtọ́kasí agbábọ́ọ̀lù alápẹ̀rẹ̀ ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
jẹ́ agbábọ́ọ̀lù alakan ará Amẹ́ríkà.Ìtọ́kasíàwọn agbábọ́ọ̀lù alakan ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Lee Louis Daniels (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ Kẹrìnlélógún Oṣù kejìlá Ọdún 1959) jẹ́ òṣèré, olóòtú, atọ́kùn àti olùdarí sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà.Àwọn Ìtọ́kasíàwọn olùdarí Qat ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
kọbè Bean Bryant (23 AUG Ọdún 1978 – 21 Jan Ọdún 2020), tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ n "Black Mamba", jẹ́ agbábọ́ọ̀lù alápẹ̀rẹ̀ ọmọ orílẹ̀ ède AMẸ́RÍKÀ.Ìtọ́kasí agbábọ́ọ̀lù alapẹrẹ ará ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Jennifer Lynn múniz (orúkọ àbísọ rẹ̀ ní Lopez; tí a bí ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù keje ọdún 1969) jẹ́ akọrin, òṣèré àti Olùdánilárayá ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.Àwọn ìtọ́kasí Jennifer Lopez net worth, age, birth, career, Wiki, Husband, Kids, family, síbílings, Fáctàwọn òṣèré fíú ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Dorothy Jean danedgbu- (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹsàn-an Oṣù kọkànlá ọdún 1922 – ọjọ́ kẹjọ Oṣù Ke-an 1965) jẹ́ òṣèré-bìnrin àti akọrin ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà, òun sì ní ọmọ Adu-Amẹ́ríkà àkọ́kọ́ tí wọ́n dáyà fún ẹ̀bùn ARIṣe fún òsèré-bìnrin tó dára jùlọ.àwọn Ìtọ́kasíàwọn akọrin ará Amékawọ́n ọmọ Áfríkà Améka òṣèré kan fi ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Damáàski () jẹ aṣọ aworan odi lati SIilki, irun ẹran, Lineni, òwú, tabi 0b013etic fiìdáná, to ni aworan hinun.Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Glasgow (; ; ) ní ìlú tótóbitó ní orílẹ̀-èdè Skokẹ́ta àti èyí tótóbitó kẹta ní Briẹ̀dá.àwọn Ìlú..
wikipedia
yo
(Ọjọ́ìbí February 16, 1959) jẹ́ àgbà tí ara Amẹ́ríkà tó wà ní ipò kínní lagbaye tẹ́lẹ̀.Ìtọ́kasí àwọn agba òje ara Américo a rubella Améls AC A idije Wimble..
wikipedia
yo
Ilie "Nasty" Nastase (, born July 19, 1946) is a Romanian former World No..
wikipedia
yo
1 Professional Tennis Player, One of the World's Top Pprs of the 1970s..
wikipedia
yo
He is one of the five dagbars in history to win more than 100 ATP professional titles (58 Singles and 45 in Doubles)..
wikipedia
yo
jẹ́ àgbà Tẹnis tó wà ní ipò kinni lágbáyé tẹ́lẹ̀.Ìtọ́kasíàwọn àgbà tísáwọn ayori Open Américowọn a Àṣẹ Fránsìàwọn àgbà tẹnis ara Romania..
wikipedia
yo
rnrn rune borg (; born 6 June 1956) is a former world no..
wikipedia
yo
Between 1974 and 1981 he wọ́n 11 Grand SIslam Singles titles..
wikipedia
yo
He won five consecutive Wibledon Singles titles and six French open Singles titles (second only to Rafael na)..
wikipedia
yo
He is considered by many to be one of the greatest Tennis Pinrs of all time.Ipò agba tẹnis ara Swídìnàwọn ayori open Fránsìàwọn a yori wíblebledon..
wikipedia
yo
Patrick Michael "Pat" Mọ́mìlo (born 28 December 1972) je agba Kabes to wa ni ipo kinni lagbaye tẹlẹ.Awon agba Tẹnis ara Australia..
wikipedia
yo
Gustavo Kuhúlì (; Born September 10, 1976) is a reTired former World No..
wikipedia
yo
He won the French Open three times (1997, 2000, and 2001), and was the Tennis Masters Cup Champion in 2000, becoming the only player to defeat pète sampras and André agassi in the same major tournament.Ìtọ́kasí.Awon ayori open Fránsìàwọn ara brasi agba Taṣàwọn agba Tẹnis ara Brasil..
wikipedia
yo
Sunday Bada (22 June 1969 – 12 December 2011) was a Nigerian sprinter who ununzed in the 400 metres event..
wikipedia
yo
He won three pẹ̀pẹ̀ther at the world indoor Championships, including a gold Medal in 1997..
wikipedia
yo
His personal best time was 44.63 ìdárayáds, and with 45.51 ìdárayáds Indoor he holds the African Indoor record..
wikipedia
yo
He set a National record in the 4 × 400 metres relay at the 2000 Olympics, where the Nigerian team also won gold pẹ̀pẹ̀st after the disCHA of the USA.Ìtọ́kasí to gba eso wúrà látinú fun Naijiria..
wikipedia
yo
Joseph Ddara tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kẹfà ọdún 1973 (19th June 1973) ní Ìlú Àbújá, Olú Ìlú Orílẹ̀ Èdè Nàìjíríà, ṣùgbọ́n tí ó jẹ́ Ọmọ bíbí Ìlú Àgbádárìgì ní Ìpínlẹ̀ Èkó jẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá ọmọ orílẹ̀ ède Nàìjíríà..
wikipedia
yo
doṣù Joseph wà lára àwọn ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù Olimpiiki fún Orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n gba amin ẹ̀yẹ Wúrà ní Atlanta lórílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà lọ́dún 1996.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Abiodun Obafemi (ojoibi 25 December 1973 ni Lagos) je agba boolu-ẹlẹṣẹ̀ ara Naijiria..
wikipedia
yo
O je agbeyin to gba opo boolu re ni Jermani, o si je omo-egbe agba boolu to gba eso wura fun Naijiria ni olimpiki 1996.Ìtọ́kasí ara-ẹlẹ́sẹ̀ ara Naijiriàwọn to gba eso wura fun Naijiria..
wikipedia
yo
Blessing ọkàgba (ojoibi 9 October 1988) jẹ́ eléré-ìdárayá orípápá ara Nigeria nínú ìfọjìnnà àti ifo ibẹ̀mẹ́ta àti erésísá ìtòsí.
wikipedia
yo
Ni Kínní ọdun 2022, o ti daduro fun odun mewa 10 fun dóping.Ìtọ́kasí to gba eso onídẹbaba ọ̀fẹ́ fun Naijiria..
wikipedia
yo
Paramore jẹ́ ẹgbẹ́ olórin Gẹ̀ẹ́sì Rock, ó jẹ́ Diddásílẹ̀ ní USA ní 2004 bẹ Hò ó jẹ́ ìkan nínú àwọn olórin tó yọrí sí rere jùlọ àti ti ó gba àyẹ̀wò dáada jùlọ nínú ìtàn orin Togbajú.Discoystuoudi Albums All wẹ́ Know Is Falling (2005) Riot! (2007) Brand New Eyes (2009) paramore (album) (2013)ẹ The Summer tic EP (2006) LangSung (2006 In THE UK 2008 (2008) The Final Rio Riot (2008) Àwọn Olorin..
wikipedia
yo
Florence DeLorez Griffith Joyner (December 21, 1959 – September 21, 1998), bakanna bi Flo-jo, jẹ elere idaraya ori papa ara Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Wọ́n gbàá gẹ́gẹ́ bí “obìnrin tó yára jùlọ títí ayé” nítorí pé àwọn rẹ́kọ́ọ̀dù àgbáyé tó dá ní 1988 fún ìsáré 100 m àti 200 m kò tíì yípadà, kò sì ti sí ẹni tó lè yípadà..
wikipedia
yo
O se alaisi lojiji loju orun nitori wárápá to gbée ni odun 1998 nigba to je omo-odun 38..
wikipedia
yo
Yunifásítì Kalifóníà ní Los Angeles (ucla) ló ti parí ẹ̀kọ́ rẹ̀.Àwọn ìtọ́kasíàwọn tó gba èso wúrà túmọ̀ fún orílẹ̀-èdè Américowọn tó gba èso fàdákà látinú fún orílẹ̀-èdè Américo ka kúkúrú..
wikipedia
yo
Asafa Powell, CD (ọjọ́ 23 November 1982) jẹ́ Ásérè ará Jàmáíkà yó gba eso Wúrà olimpiki.Ìtọ́kasíàwọn ara Jamaia tó gba eso Wúrà ọkùnrin fún Jàmáíkà..
wikipedia
yo
jẹ́ Ásérè-ìdárayá ará Jàmáíkà yó gba èso wúrà ọ̀fẹ́.Àwọn ará Jamaiwọ́n tó gba èso wúrà ọ̀fẹ́ fún Jàmáíkà..
wikipedia
yo
Yohan Blake (Ọjọ́ìbí 26 December 1989) jẹ́ Rerèìdárayá ara Jàmáíkà yo gba eso wúrà látinú.Àwọn ara Jamaia tó gba èso wúrà fún Jamaiwọn tó gba èso fàdákà fún Jàmáíkà fún Jàmáíkà..
wikipedia
yo
Olapade Adeniken ti won bi ni ojo kokandinlogun osu kejo odun 1969 (19th August 1969) ni ilu Oso) asare feyinti elere idaraya omo orile-ede Naijiria ti o maa sare iwon ogorun-un mita ati igba mita..
wikipedia
yo
Oun ni baba Michael Adeniken.O ti sare gbamin eye baba ninu ere idije 4 × 100 m relay pelu awon akegbe re, Chidi glutamic, Oluyemi Kayode ati ọgọ́sán Eonawawa..
wikipedia
yo
Ni ìdíje Olimpiiki ti wọn se lodun 1992 ni ilu Barabinrinru ni orile ede Spain oun ni omo Naijiria akoko ti o sare iwọn mita ogorun-un láàarín iṣẹju-aaya mẹwàá..
wikipedia
yo
Oun naa lo tun pa aṣeyọri yii rẹ pẹlu iṣẹju-aaya mẹsan-an o le diẹ lọ́dún 1994..
wikipedia
yo
asare dije oluṣọji fádepo (9.85 S) ati ọgọ́sán Ehatwa (9.94 s) ni o tun ggede ju u lo ni iwọn akoko si sare iwọn mita ogorun-un.Awon itọkasiàwọn elere-idaraya ara Naijiribọ̀wọ̀ ọmọ Yorùbá..
wikipedia
yo
Victor Chinedu Anikàyéfì (ọjọ́ 23 April 1988) jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá ní orilede Nàìjíríà, àbí arákùnrin Victor Anikàyéfì sí Ìlú Èkójipọ̀àwọn tó gba eso fàdákà látinú fún Naijiriẹsẹ̀ agbabọọlu-ẹlẹ́sẹ̀ ara Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Onyekachi apam (ti a bi ni ojo ogbon osu kejila, odun 1986 ni Aba) je agbaboolu ile Naijiria ti tele ti o fẹyìntì ni odun 2014 leyin ti o farapa nigba ti o nsiré fun Seattle sóunders FC..
wikipedia
yo
Ó ṣe aṣojú Nàìjíríà ní ọdún 2008 Summer Olympics ní ìlú Beijing gẹ́gẹ́ bí apá kan ti ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àwọn ọkùnrin.Iṣẹ́ rẹni ọdún 2005, àpam gbìyànjú fún Oghic Nice, níbití ó ti f'ọwọ́ sí nígbà náà..
wikipedia
yo
O ṣe awọn ifarahan 105 ati paapaa faagun adehun rẹ lati pari ni ọdun 2013 to yẹ ko jẹ ọdun 2012 ṣaaju ki o to lọ si Stade Rennes ni ọdun 2010.Awọn itọka si..
wikipedia
yo
Oluranmisí Kayode jẹ asare ori ọdán ọmọ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Wọ́n bí ní (July 7, 1968– October 1, 1994).17 jawe olubori ninu ifese-wọnsẹ̀ 4 ×100m nínú idije tí idije ti 1992 Olympic Games ní Barcelona, oun pelu iko rẹ Chidi Adeni ati ọgọ́sán E-D..
wikipedia
yo
O tun gba ami Silver Medal ninu 200 metres nibi ìdíje 1993 African Championships oun nikan si ni ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà tí ò tíì gba irúfẹ́ àmì ẹ̀yẹ yìí nínu irú ìfẹsẹ̀-wọnsẹ̀ yí ní ọdún 1993 àti 1994..
wikipedia
yo
O gbe ipo kẹfa ninu ìfẹsẹ̀-wọnsẹ̀ ti 200 metres ninu ìdíje 1994 Commonwealth Games..
wikipedia
yo
Káyọ̀dé kú nínú ìjàǹbá ọkọ̀ ní Northern Arizona ní Oṣù October 1994..
wikipedia
yo
Wọ́n sọ pápá ìṣeré kan ní orúkọ rẹ̀ ní ìlú Adó-Èkìtì ní Ìrántí rẹ̀.Àwọn ìtọ́ka síàwọn tó gba ẹ̀ṣọ́ fàdákà ọ̀fẹ́ fún Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Faakotu ogunkoya (Ọjọ́ìbí 5 Dec 1968) je Ara-ìdárayá to gba eso fadaka ninu ifese ninu ifese igbá atix ati esobaba jade ninu ifesebo 400 m ni idije Omupo ni Atlanta awon itọkasi.Awon to gba eso fadaka lati gba Naijiria to gba eso ko si Naijiria fun Naijiria..
wikipedia
yo
ChiBQ Okonkwo (ọjọ́ 16 December 1988) jẹ́ agbá bọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ ará Nàìjíríà tó ungba bọ́ọ̀lù lọ́wọ́lọ́wọ́ fún Enugu RangersÌtọ́kasí.Àwọn tó gba èso fadaka olimpiki fún Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Isaac Promise tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejì Oṣù kejìlá ọdún 1987 tí ó sin di olóògbé ní ọjọ́ kejì Oṣù Kẹwàá ọdún 2019 (2 December 1987 - 2 October 2019) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà , agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá..
wikipedia
yo
òun ni adarí ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá ọkùnrin tó sojú orílẹ̀ èdè Nàìjíríà nínú ìdíje Olympic ọdún 2008, tí wọ́n sin gba ipò kejì pẹ̀lú ìfẹ́-ẹ̀yẹ fàdákà wa sílẹ̀ láti ìlú Beijing..
wikipedia
yo
Ó gbá bọ́ọ̀lù jẹun fún odidi ọdún mẹ́rìnlá, púpọ̀ nínu ọdún tó lọ gẹ́gẹ́ bí agbábọ́ọ̀lù tó peregedé ní ó lò ní orílẹ̀-èdè Turkey..
wikipedia
yo
O ti gba iye bọ́ọ̀lù tí ó tó mẹ́tàdínlọ́gọ́rin (77) wọlé sáwọn nígbà ayé rẹ̀.Àwọn ìtọ́kasíàwọn tó gba eso fàdákà látinú fún Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ambruse Vanzekin (ọjọ́ 14 July 1986) jẹ́ aṣọ-ojúlé bọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ ara Nàìjíríà tó úngba bọ́ọ̀lù lọ́wọ́lọ́wọ́ fún Warri Wolves f.C..Ìtọ́kasí tó gba eso fàdákà ohùn fún Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Fatima Yusuf-Olukokoju (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejì 2 Oṣù Kàrún-ún, Ọdún 1971 ní owó, Ìpínlẹ̀ Òndó) jẹ́ asare Nàìjíríà tó ti fẹhinti, tó sáábà máa n díje ní 400 mitasi ní gbogbo ìgbà tó ń sáré..
wikipedia
yo
Ó gba ipò kìíní ní ìdíje 400 mítàsí ní 1991 All-Africa Games àti ipò kejì ní ìdíje 200 mítàsí..
wikipedia
yo
O fẹ́ Adewale olùkọ́jú.ayé rẹ ò padà díje ní 200 mitasí, ìdíje ti gbogbo ayé ní Spain níbi tó ti ṣa 22.28 ìṣẹ́jú-àáyá..
wikipedia
yo
Òun náà tún ní obinrin àkọ́kọ́ ní ilẹ̀ Adúláwọ̀ láti sáré lábẹ́ aadọta ìṣẹ́jú-àáyá ní 400 mitasí..
wikipedia
yo
O ṣa 49.43 iṣẹju-aaya ni ọdun 1995 ni idije to waye ṣaaju awọn Adulawo..
wikipedia
yo
O dije fun Naijiria ni Suma OganganKíṣì ti ọdun 1996 ti won se ni Atlanta United States ni 400 mitasi nibi to ti gba ipo kẹfa pẹlu iṣẹju-aaya 49.77 ati 4 × 400 mitasi nibi to ti gba ẹbun fadaka pẹlu awọn akegbe rẹ Bisi Abibibi, Charity Opara ati Fonalat Ogunkoya leyin ilu America to gbe idije naa kale..
wikipedia
yo
Ó lọ sí Azusa Pacific University.Ìtọ́kasí DatabaseOlympics Àwọn tó gba eso fàdákà látinú fún Nàìjíríà..
wikipedia
yo
(December 20, 1914 – July 30, 2013) jẹ́ olóṣèlú ará Amẹ́ríkà àti ní Ilé Alàgbà Amẹ́ríkà tẹ́lẹ̀.Ìtọ́kasí ̀sèlú ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Queen jẹ ẹgbẹ olorin Geesi Rock, O jẹ́ Diddásílẹ̀ ní London ní 1970.Discography (19731973)Queen II (1974)Shr. heart attack (1974)a Night at the opera (1975)A Day at the Races (1976)News of the World (1977)Jazz (1978)The Game (1980)flash Gordon (1980)Hot Space (1982)The Works (1984)A kind of Magic (1986)The Miracle (1989)Inṣèèyàn (1991)made) in Heaven (1995)àwọn ẹgbẹ olórin..
wikipedia
yo
Frank Raleigh Lautenberg (; January 23, 1924 June 3, 2013) jẹ́ olóṣèlú ará Amẹ́ríkà àti ní Ilé Alàgbà Amẹ́ríkà tẹ́lẹ̀.Ìtọ́kasí ọ̀dalúlú Ara Américo alàgbà aṣòfin Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà láti New Jersey..
wikipedia
yo
(1917-2010) jẹ oloselu ara Amẹrika ati ni Ile Alàgbà Amẹrika tẹlẹ.Ìtọ́kasíàwọn oloselu ara Amẹrika..
wikipedia
yo
(1924-2012) jẹ́ olóṣèlú ará Amẹ́ríkà àti ní Ilé Alàgbà Amẹ́ríkà tẹ́lẹ̀.Ìtọ́kasíàwọn olóṣèlú ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
(1932-2019) jẹ oloselu ara Amẹrika ati ni Ile Alàgbà Amẹrika tẹlẹ.Ìtọ́kasíàwọn oloselu ará Amẹrika..
wikipedia
yo
(1942-) jẹ́ olóṣèlú ará Amẹ́ríkà àti ní Ilé alàgbà Amẹ́ríkà tẹ́lẹ̀.Ìtọ́kasíàwọn olólúlú ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo