cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
O tun lọ pọpọ orin, o dapọ Ìjẹ̀bú-Ìjẹ̀ṣà Choral ohun pupọ-pupọ pẹlu awọn orin aladun ati ọrọ lati awọn orisun Kristiẹni.Ni ọdun 1962, o tu orin silẹ 'Salome' labẹ awọn igbasilẹ Decca..
wikipedia
yo
Orin naa dapọ awọn èròjà ibile ni asa Yoruba ati igbesi aye ilu bi awon akori pataki..
wikipedia
yo
Orin miiran ti Tire eyiti o gbajumọ jẹ ka Sora (jẹ ki a Sora), orin naa ni a ṣe apejuwe nigba miiran bi asọtẹlẹ ti ogun abẹlẹ Naijiria ninu ikilọ rẹ nipa awọn ìpọ́njú ti ijọba ti ko ni ìrònú..
wikipedia
yo
O tun tu awọn gbajugbaja olokiki miiran pẹlu ọkan nipa Oloye Awolowo, eniti o wa ninu tubu ni akoko orin ti tu silẹ.Awọn ohun elo ẹgbẹ naa lo ilọsiwaju ACCordion, eyiti o dun nipasẹ I.K., ati pe o jẹ akọrin olokiki giga akọkọ lati ṣe akopọ..
wikipedia
yo
Awọn ohun elo orin miiran ti ẹgbẹ naa lọ pẹlu, gìta ina, ilu ti n sọrọ, ohun iṣere meji, Aaku, Onai, Awọn age, Maracas, agogo ( agogo ), Samba (Ilu onigun mẹrin).Ìgbésí Ayé nigbamii iduro Dairo ni oke ni ipele orin Naijiria jẹ igba diẹ, nipasẹ 1964, akọrin tuntun; Ebenezer Obey; ti n gba ile ati ni ipari awọn ọdun 1960, mejeeji Obey ati King Sunny ti farahan bi Awọn iṣẹ olokiki ti akoko naa..
wikipedia
yo
Sibẹsibẹ, Dus tẹsiwaju pẹlu orin rẹ, irin -ajo ni Yuroopu ati Ariwa America ni awọn ọdun 1970 ati 1980..
wikipedia
yo
Ó tún kópa nínú àwọn ẹgbẹ́ ìjú díẹ̀ tí ń dáwọn pẹ̀lú àwọn ètò ohun -ìrì ti àwọn akọrin..
wikipedia
yo
Laarin 1994 ati 1995, o je omo egbe ti EthnoMusicology ni University of Washington, Seattle.aworan alaworan ti I.K..
wikipedia
yo
Vúsá ati àwọn aaye dudu CD aṣhiko , 1994, Orin XÉléphile De Definitive , Orin XÉléphile Mo rántí , orin ti Àgbáyé ti Titunto Jùjú , Orin atilẹba ‘Àwọn igbasilẹ' Salómè Sack 92 ní Mo ori Mimí ni mo nṣe Mo rántí olùfẹ́ Mi , Opòkìkíra Dte Jaiye J ṣe b'Olúwa Lo'Olúwa npèsè Ìṣọ̀kan Yorùbá Mo ti yege ní yege.K..
wikipedia
yo
Ni ọdun 1960, lakoko ayẹyẹ ominira Naijiria, a pe ẹgbẹ naa lati ṣere nibi ayẹyẹ ti gbajugbaja kan [[Ibadan] ] Agbẹjọro ati oloselu Oloye Doa Oguntóyè..
wikipedia
yo
Dairo ṣe afihan ara rẹ ti orin Jùjú ati gba akiyesi ati iwunilori lati ọdọ awọn alabojuto Yoruba miiran ti o wa, ọpọlọpọ ninu wọn nigbamii pe e si awọn ere orin lakoko awọn ayẹyẹ aṣa tabi awọn ayẹyẹ lasan..
wikipedia
yo
Lakoko àsikò naa, o ni anfani lati ṣe aami igbasilẹ tirẹ ni ifowosowopo pẹlu Haruna Ishola ati ṣaṣeyọri pataki ati olokiki olokiki ati olokiki.ipa ati awokọṣe ik Dairo farahan ni ipari awọn ọdun 1950 ni ibamu pẹlu Ẹupria ti ṣaaju si ominira..
wikipedia
yo
O tun lọ pọpọ orin, o dapọ Ìjẹ̀bú-Ìjẹ̀ṣà Choral ohun pupọ-pupọ pẹlu awọn orin aladun ati ọrọ lati awọn orisun Kristiẹni...
wikipedia
yo
Sidney Eoriode Esiri je olorin omo orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
A bíi ní ọjọ́ kinni oṣù karun-un ọdún 1980 ni Ikeja, ìpínlè Èkó, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O si tun jẹ ẹni ti o n kọ orin silẹ ti o tun jẹ akọrin.Igba ewe rẹ Dr Sid wá lati Ipinle Delta ,ṣugbọn Ipinle Eko ni wọ́n bi si ti o jẹ́ ti ṣe kékeré..
wikipedia
yo
Ìyá rẹ̀ jẹ́ amúnidara tí bàbá rẹ̀ sì jẹ́ agbá òsèré ti ótilé jùstus Ésírì tí ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ "Order of the Niger (Mon)" ó tún jẹ́ olókìkí nínú ipa kan tí ó kó nínú orí rẹ̀ ìtàgé kan tí ó sì ṣe é,èyàn eré kan tí óyin ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ọdún 1980..
wikipedia
yo
Sid jẹ́ ọmọ Ikeji nín àwọn mẹ́rin tí Obirine bí.Láti ìgbà èwe rẹ̀ lọ́tì fẹ́ di ó ní entertainer ,ṣùgbọ́n nkan yí padà bí ó ṣe jáde ilé ìwé mẹsan ní Nàìjíríà AirForce ìyẹn ilé ìwé àwọn ẹ̀ṣọ́ òfúrufú[3] ni Ikeja ti òjé òlùlù ìpínlè Èkó ..
wikipedia
yo
lẹ́yìn gbà ná ni ó lọ sí ilé-ìwé gíga University of Ìbàdànní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ láti lọ ka ìmọ̀ ẹ̀kọ́ nípa ẹ̀yin kí olèdi Dókítà ẹlẹ́yin..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bí ẹ ní tí ó fẹ́ràn eré ìdárayá ,ṣe ni ó kọ́ pa ní ijó jíjó, eré orítage ní ilé ìwé Be Nani ó gba àwọn ẹ̀bùn tí ó pọ̀ jantirẹrẹ.Iṣẹ́ rẹni ọdún 1999 Dr Sid darapọ̀ mọ́ Trybe Records tí wọ́n da ẹgbẹ́ Trymenmen ti Nàìjíríà hip Pop, ti Sid sì jẹ́ akọrin..
wikipedia
yo
Osu fi òdú meta fi ma jo fun egbe TrybeKókóen.Ni odun 2002 Dr Sid padà di ẹni ti o fi ero ohun leyin igba ti o dara po mo egbe da Trybe won si tun fun ni afani lati darapò mó orin kan ti akole re je "oya, Sa Sha,2-Shitz,del,del ti o si fi da rògbòdiyàn larin awon akorin(Hip Pop) ni ọdun 2002..
wikipedia
yo
lẹ́yìn ìgbànã Sid gbé orin títí ẹ jáde tí àkọlé rẹ̀ sì jẹ́ "Dont Stop" tí ó sì jẹ́ alákọ́kọ́ nínú mẹwa tí wọ́n gbọ́ tí wọ́n sì fi ṣe àfihàn rẹ̀ lórí ḿbi fún ọ̀sẹ̀ mẹ́jọ..
wikipedia
yo
Ó dá iṣẹ́ orin kíkọ dúró láti filé parí ìmọ̀ rẹ̀ ní ilé ìwé gíga Fásitì.Ní ọdún 2004 Dr Sid di Dókítà ẹlẹ́yin .Tí ó sì lọ sí ìlú Òyìnbó tí ó sì bá àwọn olórin kan ṣiṣẹ́ bí,JJc àti 419 Squ, Felix Olùjẹ̀, Kasten, R7070, D'Prince àti D'Ban..
wikipedia
yo
Ni igba ti o pada si ile Naijiria ,odarapo mo Lagos State Teaching Hospital, leyin igbana ni olo fun Àgùnbánirọ̀ ni ilu Léku ni Ipinle Adamawa..
wikipedia
yo
Sid bá oríṣiríṣi ilé-iwosan tí wọ́n tó ẹ̀yìn ṣiṣẹ́, tí ó sì ń bá iṣẹ́ orin ẹ̀ lọ.Ní ọdún 2005 ní ọdún yí Sid bẹ̀rẹ̀ sí losi Chep Studio tí osi gbé àwo kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ "Progsis " tí ó ṣe afihan "Raise dá Rọf" nínú àwo náà..
wikipedia
yo
Wọ́n mú fún ẹ̀bùn kan gẹ́gẹ́ bí olórin tí ó ṣebẹ́rẹ́ tí ó sì gbà láti àwọn tí wọ́ da ayẹyẹ Le (Tgaines Award ) ní ọdún 2006 ó gbé orin awo yí kalẹ̀.Ní ọdún 2007 lẹ́yìn ọdún mẹ́ta , Dr Sid ro pé ohun yí ó fi iṣẹ́ ìtọ́jú ẹ̀wé kalẹ̀ tí ó sì gbajúmọ̀ iṣẹ́ orin ní kíkọ tí Don jazzy sí gbà wọlé tí ó sì tún ṣe àwo kan tí àkọ́lé rẹ̀ sì jẹ́ “ Curricm Vitae “Ẹ ní abẹ́ Mo HIPtz All ..
wikipedia
yo
Tí ó sì ṣe àfihàn márùn di lógún orin sí inú rẹ̀ tí "Booty call àti close to you " jẹ́ kan lára ẹ̀.Ní ọdún 2009 Dr Sid bẹ̀rẹ̀ sí ní kọrin bí akọrin sólo ní abẹ mọ́'hits Records tí Don Jazzy jẹ́ producer rẹ̀..
wikipedia
yo
Àkọ́kọ́ nínú Albumú yí ,tí àkọlé rẹ̀ síjẹ̀ "Something about you" tí ó sì jáde ní ọdún 2009 tí ósì gbé àwọn aláwọ̀ dúdú ga àti Winchi Winchi àti Wande Coat àti Pop Something ft D'Ban kọ..
wikipedia
yo
Dr Sid gba àmì ẹ̀yẹ láti ọwọ́ MTV Africa Music Award ní orílẹ̀ èdè Kẹ́nyà gẹ́gẹ́ bi ọmọ ẹgbẹ́ Mo'hitz àti D'Banj] Wande Coana ni wọ́n jọ gba àmì ẹ̀yẹ yi.Ní ọdún 2014 ní ọdún yí wọn tí mo Dr Sid tí Moses InW ṣe àfihàn rẹ̀ nínú orin kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ "The Last 3 dígí “ ”
wikipedia
yo
Nonso Dioub se afihan rẹ ninu ere ori itage kan ti akọle rẹ jẹ "NYSC Corp member ti Ere yi si gba ere ti o daju n ile oya ni ọdun yi ni Parisi orile ede France..
wikipedia
yo
2013 West African rẹmixi Prince, Sarko, Womi, Spiper Adab, and Lynx Jazzy Dan The With East African African bony Mae Jazzy the Withes Ape Sanp Beatdu Don Don Dada Javka Mel M&sig Javted Jazzy Jadu Moroko Na Javlope Mopuv Nav bon (Don Javlope Jazzy Jazzy Jansesi Motes Savage Jazzy Dakini Ọdun 2015 Ni Oko Kabiyesi Jazzy Jazzy Best Jazzy Do2] Jace Oroko from things: Oroko Uamo Uv Jazzy N Close Ja Jazzy and Al Oroko. N- Lati Eœls N Eaila ed, Shody, Sode Goriy Nid Ni Shaka Sangun OST O Di Àkójọ Ọdun ti Di La 2016 jade ati awon oludari Reun Rewi Stope M About Ruse Ogun Ouse E the Moon/ N Something ft D' ìkórìíra M'Ore Oho ft Dalu Eho 2017. Ogun O 2016 N 2016 Egba Fi 2017/A-irin/ N Kan Mo 2 ton Oroko Tad Productions N M O to Al Da Dabu To O ode Na TV 2 ft Jazzy Uسن from iwe iwe ojogbon ISBNr Coov/ Ni M to Talk to Talk Tiwa N Best Peters & Best F F Belka Bellola E ta Meta Meta Me Kan Mogo Tata M and Close Me & A- O ti gba ami-Olukuluku ti gba 2008 Ha O Mi O 2016 Video Awards Video 2016 & W[2] Ni Oluce to the Year & B & ↑ M Single ''*_
wikipedia
yo
Maobilẹ́kọ̀ọ́ Innoatké, tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Majek Fashek jẹ́ olùkọ́ orin, atajì àti olórin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Fashek yan ìlú Benin láàyò lọ́dọ̀ ìyá rẹ̀ lẹ́yìn ìgbà tí bàbá àti ìyá rẹ̀ kọ ara wọn sílẹ̀, tí ó sì dára pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ akọrin Ìjọ Alágbára kan, níbíntì ó kọ́ bí wọ́n ṣebn lu ìlù àti àwọn ohun èlò orin mìíràn, tí ó sì ń hun orin fún àwọn akọrin ijó náà.Iṣẹ́ orin rẹ̀nípa torin, a lè sọ wípé Majek ní àrólé fún olóògbé Bob Marleyley, nítorí gbogbo ìwọ́hùn olóògbé náà ní Fashek mú pátá..
wikipedia
yo
Ó wà lára ọ̀kan pàtàkì nínú àwọn ọmọ bíbí ilẹ̀ [Nàìjíríà]] tí gbé orin reggae tí ó ti ilẹ̀ Caribbean wá..
wikipedia
yo
Àmọ́, lọ́wọ́ kí Majek ó gbagbe ilé àti orin ìbílẹ̀ wa pata, ń ṣe lọ mú ọnà orin bíi Fuji àti Jùjú mọ́ orin reggae tí ó sí tibẹ̀ fa ọnà orin tire tí ó pè ní Koloolooloolo yọ lọ́ẹ̀ ara.IKÚ rẹ̀Majek kù sí ojú orun rẹ̀ ní Ọjọ́ kejì Oṣù kẹfà ọdún 2020 sí ìlú New York.Awon ìkànka sí àwọn Ọjọ́ìbí ni àwọn olórin ara Nàíjíríà..
wikipedia
yo
Pshasha Henry Zamani, tí orúkọ orí ìtàgé rẹ̀ ń jẹ́ Ice Prince ni a bí ní ọgbọ̀n ọjọ́ Oṣù Kẹwàá ọdún 1984..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ akọrin hip hop ọmọ [[Nàìjíríà tí o n kọ orin sílẹ̀ tí o tún ṣeré orí ìtàgé..
wikipedia
yo
Òkìkí rẹ̀ kàn nígbàtí ó gbé "Olèkú", síta, orin náà jẹ́ ọ̀kan lára orin tí wọ́n ṣe àdàlú rẹ̀ jùlọ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O gba ipo kini ni ọdun 2009 ni Hennessy artistry Club tour..
wikipedia
yo
Orin akọkọ rẹ ni yàrá ìtẹ́ orin sita ti o pe ni gbogbo eniyan fẹran ice Prince jade ni ọdun 2011..
wikipedia
yo
Ni ojo kinni osu keje odun 2015, won kede ice Prince gege bii igbakeji Aare chocolate City..
wikipedia
yo
O di oye naa mu titi di igba ti o fi akẹ́kọ̀ọ́ku naa sile ni odun 2016.itọkasi awon olorin ara Naijiria..
wikipedia
yo
Innocent Ujah Idibia (tí a bí sí ìlú Jos, ìpínlẹ̀ Plateau State, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí orúkọ inagijẹ rẹ̀ n jẹ́ 2baba, jẹ́ olórin orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, akọrin sílẹ̀, àgbọ̀rín jáde àti oníṣẹ́ àdáni..
wikipedia
yo
Ní Oṣù Keje Ọdún 2014, ó yan 2face Idibia gẹ́gẹ́ bi orúkọ ìtàgé rẹ̀..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olórin ilẹ̀ Áfíríkà tó ń kọ orin Afro Pop tí ó lọ́lá jùlọ tí ó sì gbayì.Ó ti lé lógún ọdún tí 2Baba ti ń kọrin tí ó sì ń dánilárayá ó sì jẹ́ ògbóǹtarìgì síbẹ̀.Ó tún jẹ́ onínúdídùn ọlọ́rẹ.Ìgbésí ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹa bí Innocent Idibia sí ìlú Jóṣ, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O je okan lara awon omo Idoma ni apa guusu ile Naijiria..
wikipedia
yo
O lọ si Mount Saint Gabriel's Secondary School ni ilu adari, Ipinle Benue..
wikipedia
yo
Ó tún lọ sí Institute of Management & Technology (IMT) ní Ìpínlẹ̀ Ẹnúgu níbi tí ó ti gboyè National Diploma nínú Business Administration and Management..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó wà ní Imt, ó maa ń kọrin níbi ayẹyẹ àti àwọn ilé-ìwé gíga bíi University of Nigeria Enugu State University of Science & Technology..
wikipedia
yo
Kò parí ẹ̀kọ́ rẹ̀, ó kúrò nílé-ìwé ó sì gbajúmọ̀ orin kíkọ.Ní ọdún 1996, ó yan “2face” gégé bíi orúkọ ìtàgé rẹ̀..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2016, ó yí orúkọ ìtàgé rẹ̀ sí 2bàbá.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ó kọrin lẹ́yìn biṢadé Ológundé( Lágbájá) fún ọdún mẹwa..
wikipedia
yo
lọ sí ilé ìwé alakọbẹrẹ sẹntira ati ile iwe giga Prestifoto Ikeja ni Ilu Eko.Óò gbe igba orin rẹ ni 2007 ti ẹgbẹ rẹ n jẹ indigo.O para pọ̀ sise pelu Sunny Nneeji, Tosin Martins, Ayanbirin, Asa ati bebelo..
wikipedia
yo
Àkọ́kọ́ orin rẹ̀ ni mo gbàgbọ́.Ó gba àmì ẹ̀yẹ Kim láwàní ní 1998 (Most Promising Female Act of the Year) àti àmì ẹ̀yẹ obìrin olóhùn Iyọ̀ ní 2006.Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní àwọn olórin ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ti orúkọ àbísọ rẹ̀ ńjẹ́ aitu irúọbẹ̀ jẹ́ olórin ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O kọkọ gba idanimọ leyin igba ti o kopa ninu atunṣe orin "ọmọge mi" Tidara-square kọ..
wikipedia
yo
wájẹ́ tún kópa nínú orin wọn tí o gbajú gbajà tí o ńjẹ "Do Me" 🙂
wikipedia
yo
Lori, o fi ohun re kun orin "thief my keroko" ti Banky W "One naira" ti o je ti M.I ni odun 2016, wájẹ́ jẹ okan lara awon adajo merin ninu eto akoko The Voice Nigeria.. Nigeria..
wikipedia
yo
‘ jẹ́ olórin ara Nàíijjìkasí àwọn Ọjọ́ìbí ní àwọn olórin ara Nàíjíríà.. ara Nàíèjà ara Nàíè ara Nàíè tí ó tún ara rẹ̀ ní ọdún Ọ̀té ní ọdún rẹ̀ ní wọ́n kan tí ó * ní ọdún rẹ̀. Ṣẹ̀ * * ara Nàíji àwon ẹ̀ibi ní àwọn olórin kan * ' jẹ́ olórin kan ni olórin ẹ̀ji ní àwọn olórin ara Nàìjíríà ní àwọn • ìdá ọ̀èmú ní àwọn Ọ̀kọ̀pọ̀ sí ọdún rẹ̀. Àwọn * ní àwọn olórin kan * ara Nàìjíríà ní ọdún rẹ̀ ní àwọn oníka ní àwọn olórin rẹ̀ sí pẹ̀lú * * * * * ní ọdún rẹ̀. Ní ọmọ rẹ̀. Àwọn ẹ̀mú ní àwọn olórin kan ara Nàìjíríà ní ó ní ọdún Nàìjíríà ní ìdá rẹ̀. Àwọn tún sí rẹ̀ sí olórin ara Nàìjíríà ní gbogbo rẹ̀ ní àpá ara Nàìjíríà ní àwọn tún sí àwọn tún * ' jẹ́ orin ara Nàìjíríà ní ọdún rẹ̀. Àwọn rẹ̀. Àwọn rẹ̀ sí àwọn àjò ara Nàìjíríà sí gbogbo ara rẹ̀.. ] rẹ̀ sí ọdún rẹ̀ sí pẹ̀lú rẹ̀ * rẹ̀ sí ọdún rẹ̀ sí ọdún rẹ̀ sí ọdún rẹ̀ * * ní pẹ̀lú ọdún rẹ̀ sí ọdún rẹ̀ ní ọdún rẹ̀ * * rẹ̀.*_
wikipedia
yo
Peter King Adeyọyin Oṣùbu tí a mọ̀ sí Peter King jẹ́ gbajú-gbajà olórin tó jẹ́ ọmọ bíbí ilẹ̀ Nàìjíríà, tí ó mọ̀ nípa ìlò onírúurú irinṣẹ́ èlò orin.Lọ́pọ̀ ìgbà, ó fẹ́ràn láti máa fọn fèrè, tí a mọ̀ sí Saxphone, tí ó sì ma fi ń gbé orin jáde àti ìlú Jáàsì fún ìgbádùn àwọn tó ní ìfẹ́ sí irúfẹ́ orin rẹ̀..
wikipedia
yo
Peter King gbajúmọ̀ púpọ̀ láàrín àwọn ará ilẹ̀ Europe àti ilẹ̀ Amẹ́ríkà ju ilẹ̀ wa Nàìjíríà lọ pẹ̀lú orin mílíkì tó n kọ́ fáwọn olólùfẹ́ rẹ̀.Wọ́n bí Peter King ní ọdún 1938 ní ìlú Enugu, ní ìwọ̀-oorun gúúsù, ilẹ̀ Nàìjíríà, ó dàgbà sí ìlú Lokọja, ìlú Èkó àti Port Harcourt..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1957, Peter King, darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ olórin Roy Chicago ní ìlú Ìbàdàn, níbi tó ti ń lu àwọn onírúurú ìlù àti èròjà orin tó dára fún ìgbádùn àwọn tó m'ayé jẹ.Ní ọdún 1961, ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ orin ní ìlú London àti Ilé Ẹ̀kọ́ Trinity..
wikipedia
yo
Ni Ilu London yii ni King ti darapọ mọ Bayọ Martins ẹni to yan Ilu laayo ati ẹlẹgbẹ rẹ, Mike Falana to jẹ afun-fere..
wikipedia
yo
Àwọn mẹtẹ̀ẹ̀ta yí wá dá ẹgbẹ́ tí a mọ̀ sí African Mesgersgers..
wikipedia
yo
Ẹgbẹ́ African Mesgersgers yí máa ń kọrin ní àwọn ibi àkànṣe ayẹyẹ àti ibi ìgbafẹ́..
wikipedia
yo
Wọ́n sì tún ń ṣe ẹgbẹ́ fún àwọn gbajúgbajà àti ìlú mọ̀ọ́ká olórin bíi, The Four ọ̀dọ́ps, The Temptations àti Diana Ross.Ẹgbẹ́ African Mesgersgers ṣe àwo orin tó tó bíi Soùn-dín-Só..
wikipedia
yo
King, tún dá ẹgbẹ́ míràn sílẹ̀ tí ó pè ní The Blues Olupders, tí wọ́n sì rin ìrìn àjò káàkiri ilẹ̀ Europe àti apá ila-oorun AduPeter.Peter King àti ẹgbẹ́ olórin rẹ̀ padà sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ọdún 1969 tí wọ́n sì kọrin láàrin ìjà ogun abẹ́lé tó bẹ́sílẹ̀ lákòókò náà ní ìlú Nàìjíríà.Ní ọdún 1971, King padà sí ìlú London, ó sì rin ìrìn àjò lọ sí ìlú Europe, Amẹ́ríkà àti Japan pẹ̀lú àwọn ẹgbẹ́ rẹ̀ tí ó pè ní Shango..
wikipedia
yo
Ó tún ṣe agbátẹrù àwọn ẹlẹgbẹ́ orin fún Boney M, nígbà àkọ́kọ́ tí wọ́n lọ kọrin níbi ìrìn àjò káàkiri sí orílẹ̀-èdè Europe ní ọdún 1977..
wikipedia
yo
Bẹ́ẹ̀ náà ló tún ṣe àwo orin mẹsan-an míràn láàrin ọdún 1975 àti 1978..
wikipedia
yo
Ó kọ̀wé orin ìgbà lọ dé fún àwọn òṣèré àti ilé iṣẹ́ tẹlifíṣọ̀nù.Ní ọdún 1979, Ewe, King padà sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ó sì dá ẹgbẹ́ p..
wikipedia
yo
Ó ń ṣe àkójọpọ̀ orin fún eré orí ìtàgé, ó wà tún ṣe àwo orin mẹ́ta kún àwọn àwo orin rẹ̀...
wikipedia
yo
Benjamin 'Kòkòrò' Adéunun (25 February 1925 – 25 January 2009) jẹ́ olórin ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Wọ́n bí sínú ìdílé ọba ní òwò, nipinlẹ Òndó, o si di afọ́jú nígbàtí ó jẹ́ ọmọ ọdún mẹwa..
wikipedia
yo
O ṣe agbekalẹ aṣa alailẹgbẹ ti orin pẹlu ilu, ati TanBourin..
wikipedia
yo
Ni ọdun 1947 o lọ si Ilu Eko, nibi to ti pade awọn olorin ilu bii Ayinde Bakare, Bobby Benson ati Victor Oluya..
wikipedia
yo
Ni ọdun 1960 ati 1970 o ṣe ifihan nigbagbogbo lori Federal ati awọn aaye redio agbegbe, ati pe a bọ̀wọ̀ fun pupọ fun ìjìnlẹ̀ ati ogbon awọn orin rẹ.O kọrin ni ede Yoruba nipa ifẹ, owo, ija ati idagbasoke Ilu..
wikipedia
yo
Ońkọ̀wé Cyprian Ẹwen kọ̀wé kọ̀wé ìdi-àkọ tí ìgbésí ayé rẹ̀ nínú àràdà rẹ̀,”ọmọkùnrin Rwíwíwí wíd eré ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ìlú ní Nàìjíríà àti ní ní òkè òkun, ṣùgbọ́n àwọn ènìyàn tí ó lo ìdùn rẹ̀ láti ṣe nígbà ó rẹ̀, ó ní láti sún, ó sì máa ń kọrin ní ó láti rí oúnjẹ jẹ ó rí..
wikipedia
yo
Ṣugbọn, ni odun 2007 gomina ipinle Eko Babatunde Raji Fashola fun un ni ile yàrá meji kan leyin ti won pade re nibi ere ti oba Sunny Ade se..
wikipedia
yo
Kòkòrò ti kú lati aisan ti o ni ibatan gbuuru laipẹ ki o to gbejade awo-orin rẹ.itọkasi awọn afọ́jú olorinàwọn olorin ara Naijiria..
wikipedia
yo
Oluséun Anikulapo Kuti (ti a bi ni ọjọ́ kọkànlá osù kini ọdún 1983), tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ mo sì ṣeun kútí, jẹ́ gbajúgbajà olórin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
ṣeun ni ó ń daríi ẹgbẹ́ olórin bàbá rẹ̀ Egypt 80.Àwọn ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ni àwọn olórin ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ti oruko inagijẹ re n je biSade ologunde ti a bi ni ilu Eko ni odun 1960 je gbajugbaja akorin afrobeat omo orile ede Naijiria..
wikipedia
yo
Gbogbo ènìyàn mọ́ akọrin yí sí lágbájá nítorí wípé ó jẹ́ ẹni tí ó fẹ́ràn láti máa lo ìbòjú láti dáàbò bo ara rẹ̀ kí wón má lè dáa mọ́..
wikipedia
yo
O gbagbo ninu atunto ilu lati ipasẹ̀ orin kikọ.ibẹrẹ aye rẹ ologunde mu oruko inagijẹ rẹ "Lagbaja" látara "Jane Dodo" ti o tunmọ si en t o fi oju rẹ pamo..
wikipedia
yo
Orúkọ rẹ̀ yìíh hàn nínú ìmúra rẹ̀ àti ìbòjú tò fi bojú..
wikipedia
yo
Ó dá ẹgbẹ́ àkọ́kọ́ rẹ̀ sílẹ̀ ní ọdún 1991 ní ìpínlẹ̀ Èkó.Àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀ 2006 Channel O Music Video Awards - Best Marù Video ("Never Far Away") àwọn orin rẹ̀ ‘KRI', 1993 Lagbaja, 1993 cest un African thing, 1996 Me, 2000 wẹ́, 2000 wẹ́ and Me Part II, 2000 Abàmì, 2000 Africano....
wikipedia
yo
The Mother of Groove, 2005 Paradise, 2009 sharp sharp, 2009 200 million múmú (the bitter truth), 2012àwọn itọkasi àwọn Ọjọ́ìbí ni àwọn olórin ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Kevin Mcdáìd (tí a bí ní ọjọ́ keje oṣù kẹta ọdún 1984) jẹ́ akọrin ará ìlú Gẹ̀ẹ́sì..
wikipedia
yo
Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni wọ́n bí Kevin sí tí wọ́n sì tọ́ dàgbà ní ìlú England ni Newcastle upon Tyne..
wikipedia
yo
Wọ́n mú dáradára gégé bíi ọmọ ẹgbẹ́ ti British Boy band V, èyí tí ó darapọ̀ mọ́ ní ọdún 2003 pẹ̀lú àwọn ọmọkùnrin mẹ́rin mìíràn..
wikipedia
yo
Ẹgbẹ́ náà ní àpẹẹrẹ àṣeyọrí mẹ́ta ní àkókò ọdún 2004 kí ó tó di wípé wọ́n pínyà ní oṣù kejì ọdún 2005,, èyí tí kò tó ọdún kan lẹ́hìn tí wọ́n gbé orin wọn àkọ́kọ́ jáde..
wikipedia
yo
Ó ń ṣiṣẹ́ báyì gẹ́gẹ́ bíi Olùkọ́ni ti ara rẹ̀.Ìgbésí ayé rẹ̀ ní oṣù kẹjọ ọdún 2005, wọ́n kẹ̀kẹ́ rẹ̀ ninu ìwé ìròyìn The Sun gẹ́gẹ́ bíi ọ̀rẹ́kùnrin ọlọ́jọ́-pípẹ́ tíí ọmọ ẹgbẹ́ WestLife, Mark Freehily..
wikipedia
yo
wọ́n gbé àwọn tọkọtaya náà jáde lórí abala àkọ́kọ́ ti ìwé ìròhìn Attitude èyí tí ó jáde ní oṣù Kejìlá ọdún 2007..
wikipedia
yo
wọ́n ṣe àdéhùn ìgbéyàwó ní ọjọ́kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kínní ọdún 2010..
wikipedia
yo
Ṣugbọn ó tipẹ́ tí wọ́n ti pínyà.Àwọn ìtọ́kasí àwọn eniyan alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ni 1984..
wikipedia
yo
EarNest Olatunde Thomas (Tunde Nightingale) jẹ́ olórin ara Nàìjíríà.Gbajúmọ̀ Olorin, ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Earnest Olatunde Thomas, tí gbogbo èèyàn mọ̀ sí Tunde Nightingale tàbí The Western Nightingale jẹ́ Oni Gìtá Ara Tó ń kọ́ Ẹ̀yà Orin Jùjú ni èyí tó ṣe àwòṣe irúfẹ́ orin ìbílẹ̀ ti Ọ̀gbẹ́ni Tunde King..
wikipedia
yo
A bi Tunde Nightingale ni ojo kewa ninu Oṣu kejila ọdun 1922 ni Ilu Ibadan..
wikipedia
yo
Ó lọ síi ilé ẹ̀kọ́ ní ìlú Èkó, ó jẹ́ ológun, ó ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ilé iṣẹ́ rélùwé..
wikipedia
yo
Ó dá ẹgbẹ́ olórin tirẹ̀ sílẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ ẹgbẹ́ olórin mẹ́ta àti irinṣẹ́ mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ tí a mọ̀ sí gìta, tánborìn-ín àti ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀ ní ọdún 1944..
wikipedia
yo
Àsikò yi ni àwọn olórin Nàìjíríà ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀ si n lọ gìtá lati ṣe àkójọpọ̀ orin tí wọ́n bá fẹ́ gbé jáde..
wikipedia
yo