cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
LaFayette was a general in the American Revolutí-13 war and a leader of the Garde nationale during the French Revolution.In the American Revolution, LaFayette served in the Continental army under George Washington..
wikipedia
yo
Wounded during the battle of brandywine, he still managed to organize a successful rẹ̀mì..
wikipedia
yo
He served with distinction in the battle of Rhode island..
wikipedia
yo
In the middle of the war, he returned to France to négòtiate an increased French commitment..
wikipedia
yo
On his return, he blocked troops led by cornWallis at Yorktown while the Armies of Washington and Jean-Baptiste donatien de Vim, comte de Rochambeau, prepared for battle against the British.back in France in 1788, LaFayette was called to the assembly of notables to respond to the fimeric crisis..
wikipedia
yo
LaFayette proposed a meeting of the French Estates-General, where Representatives from the three traditional classes of French society — the clergy, the Jèhófàtes and the Combucks — Met.. *
wikipedia
yo
He served as vice president of the resulting body and presented a draft of the Declaration of the Rights of man and of the Citizen..
wikipedia
yo
LaFayette was appointed commander-in-chief of the French (Garde nationale) National Guard in response to Violence leading up to the French Revolution..
wikipedia
yo
During the Revolution, LaFayette attempted to maintain order, for which he ultimately was persecuted by the jacoyángá..
wikipedia
yo
In 1791, as the Radical fáctions in the Revolution grew in power, LaFayette tried to flee to the United States through the Dutch Republic..
wikipedia
yo
He was captured by Austrians and served nearly five years in prison.KFayette returned to France after Bonaparte freed him from an Austrian prison in 1797..
wikipedia
yo
He was elected to the Chamber of Deputies under the CHARter of 1815, during the hundred days..
wikipedia
yo
with the Bourbon Restoration, LaFayette became a Liberal member of the Chamber of Deputies in 1815, a position he held until his death..
wikipedia
yo
In 1824, president James Mone invited laFayette to the United States as the "Nation's guest”; during the trip, he would visit all of the then twenty-four states..
wikipedia
yo
For his akẹ́kọ̀ọ́ to the American Revolution, many cities and Monuments throughout the United States bear his name (Fayettest, North Carolina was the only one of those he actually visited in person)..
wikipedia
yo
During France's July Revolution of 1830 LaFayette declined an offer to become the French dictator; instead he bakibukited Louis-Philippe's Aurea as a Constitutional monarch..
wikipedia
yo
LaFayette Died on 20 May 1834, and is uriuri in picpus Cemetery in Paris, under soil from Revolu-13 War BalT; Bunker Hill..
wikipedia
yo
He became a natural born Citizen of the United States during his Lifetime and received Honorary United States Citizenship in 2002.Awon Ọjọ́ìbí ni 1757 Ojol ni 1834àwọn ará Fránsì..
wikipedia
yo
Allamah Rashheed Turabi (9 July 1908 – 18 December 1973) jẹ́ ẹni pàtàkì ara Pakistan ọ̀mọ̀wé, olórí ẹlẹ́ṣin , Asọ̀rọ̀ Ode, akọ àti Amòye.Ìtọ́kasí ní Ọjọ́ìbí ni níjọ́ede ní 1973àwọn ara Pakistan..
wikipedia
yo
jẹ́ ààrẹ ilẹ̀ Pakistan tẹ́lẹ̀.Ìtọ́kasí Ọjọ́ìbí ni àwọn ara Pakistan..
wikipedia
yo
jẹ́ Ààrẹ àti àpapọ̀ àgbà ilẹ̀ Pakistan tẹ́lẹ̀.Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ni àwọn ara Pakistan..
wikipedia
yo
Sardar SOOq Ahmad Khan recruhari (Punjabi, ) (May 29, 1940 – October 20, 2010)je Aare kejo orile-ede rkStan lati November 14, 1993 titi dé December 2, 1997.Ìtọ́kasí awon Ọjọ́ìbí ni 1940awon ojoaláìsí ni 2010awon ara Pakistan..
wikipedia
yo
pervez SaluMíríámù: Kaed (11 August 1943 - 5 February 2023), Ni(M), Tam-E-Salat Award, was a PaSantánì Poli and military figure who served as the tenth president of Pakistan (2001-2008) and the Chief of Army Staff of the Pakistan Army (1998-2007)..
wikipedia
yo
jẹ́ ààrẹ ilẹ̀ Pakistan tẹ́lẹ̀.Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1943àwọn ará Pakistan..
wikipedia
yo
jẹ́ Ààrẹ àti àpapọ̀ àgbà ilẹ̀ Pakistan tẹ́lẹ̀.Ìtọ́kasí Ọjọ́ìbí ni àwọn ara Pakistan..
wikipedia
yo
jẹ́ àpapọ̀ àgbà ilẹ̀ Pakistan tẹ́lẹ̀.Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ni àwọn ara Pakistan..
wikipedia
yo
jẹ́ àpapọ̀ àgbà ilẹ̀ Pakistan tẹ́lẹ̀.Ìtọ́kasí Ọjọ́ìbí ni àwọn ara Pakistan..
wikipedia
yo
O jẹ obinrin akọkọ ti a yan lati ṣe olori ijọba tiwa-n-Tiwa ni orilẹ-ede Musulumi ti o pọ julọ..
wikipedia
yo
Ni imoran ti o lawo ati aláìlèsin, o je Alaga tabi Igbakeji Alaga egbe Pakistan Peoples Party (PPPP) lati ibere awon odun 1980 titi di ipaniyan re ni odun 2007.itọkasi awon Ọjọ́ìbí ni awon ara Pakistan..
wikipedia
yo
jẹ́ àpapọ̀ àgbà ilẹ̀ Pakistan tẹ́lẹ̀.Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní àwọn ara Pakistan..
wikipedia
yo
Ogbún Davis (December 18, 1917 – February 4, 2005) je ọmọ Afrika-Amẹrika oṣere fíat, oludari fíat, akọewi, olukọere, Olukọwe, ati Aat Awujọ.Igba EweDavis jẹ bibi bi Rford Chatman Davis ni Anaat, linch County, Georgia, ọmọkunrin Kince Charles Davis, Oníṣẹ́-ẹrọ Ikọ̀ ọkọ Ojúirin, ati Iyawo rẹ̀ Laura Cooper..
wikipedia
yo
The name OIyawo came from a County Clerk who misheard his mother's Letusi of his initials "R.C.” When he was born..
wikipedia
yo
Bí àwọn òbí rẹ̀ ṣe fẹ́, ó lọ gbẹ̀kọ́ ní Yunifásítì Howard ṣùgbọ́n ó kúrò níbẹ̀ láìparí ní 1939 láti bá bẹ̀rẹ̀ síní ṣe iṣẹ́ òṣèré ní ìlú New York; lọ́jọwaju ó lọ gbẹ̀kọ́ ní ilé-ẹ̀kọ́ gbogbo ìmọ̀ Yunifásitu kọlùpajú..
wikipedia
yo
Iṣẹ oṣere rẹ, to gba Ẹ̀wádún meje, bẹrẹ ni 1939 pẹlu Rose McClendon PInrs ni Harlem..
wikipedia
yo
O se fíFI akoko re ni 1950 ninu fíFI Sidney poiTi no way Out..
wikipedia
yo
Ohun ni ohun Atinusi Idara lori ere tẹlifíṣàn awon ọmọde sesame Street lori pbs niti aworan Alamurin rè.Awon Ọjọ́ìbí ni 1917awon ojoaláìsí ni 2005awon osere ara Amerika..
wikipedia
yo
Joe “King Oliver (May 11, 1885 – April 10, 1938) jẹ́ odilá fẹ́rẹ̀ Kornet Jazz àti Olori ẹgbẹonílù..
wikipedia
yo
Àgàgà ó ṣe pàtàkì fún irú ọ̀nà tó fín fan fẹ́rẹ̀, nípa kíkọ́kọ́ lo ìdákẹ́..
wikipedia
yo
Bakanna bi alásopọ̀ orin to se pataki, o fowoko opo awon orin ti a si ńgbó loni, bi "Wuppermouth Blu", "Sweet Like this", "Canal Street Blurs", ati "Doctor Jazz"
wikipedia
yo
Ipa rẹ̀ ga tó bẹ tó ti Armstrong fi sọ pé, “Tí kò bá ṣe fún Joe Oliver, Jazz kò ní rí bó ṣe rí loni".Àwọn ará Américowọn olórin ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Lorraine HansBERRY (May 19, 1930 - January 12, 1965) jẹ́ ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà Aroko àti àfọwọ́kọ̀wé àwọn ọ̀rọ̀ olóṣèlú, Lẹ́tà, àti àròkọ..
wikipedia
yo
Iwe rẹ to gbajumọjulọ, a raisin in the sun, wa lati ibi wahala awon ebi re nile-ẹjọ nitori ofin elẹ́yàmẹyà igbẹle ni apa Washington Park ti South Side Chicago nigba to wa lọmọdé.Iji Ọjọ́ìbí ni 1930awon Ojoaláìsí ni 1965awon omo Afrika Amerisee Olukọwe ara Amerika..
wikipedia
yo
Sinai tàbí Peninsula Sinai; Sinaa; Hebrew syny) jẹ Peninsula onígunmẹ́ta kan ni Egypt tó jẹ́ bẹ̃ ..
wikipedia
yo
Ó dùbúlẹ̀ sí ãrin omiÒkun Meditaréani sí àríwá, àti omiokun pupa sí gúúsù, bẹ́ síni ohùn nìkan ní apá ilẹ̀ Egypti tó bùdó sí àsíá nìyàtọ̀ sí Africa..
wikipedia
yo
Lapapọ mo orukọ oníbiṣẹ́ rẹ, awọn ara Egypti tun pe ibẹ̀ ni "Ilẹ̀ Faaroussi ("land of Fayrouz"), toduro lori ọrọ ede Egypti Ayéun "Dumaf", to ni itumọ kanna..
wikipedia
yo
Peninsula na jẹ pinpin si ile-gomina Egypti meji, o si ni olugbe bi ẹgbẹgbẹ̀rún 1.3 Awọn eniyan.itọkasi itan ilẹ̀ Egipti..
wikipedia
yo
Sriní àìyangargar Rmanuele frs, daada bi Sriaditíaṣa iyengar Rmanuen Kaka (22 December 1887 – 26 April 1920) je ara India Oluṣèfẹ́qmátìki ati akekofúnra to, lai gba eko alamọgbese ninu Matkan ninuhiki ògidì, ko ipa pataki si Ituwo onirumathiki iro nọmba, awon ẹsẹẹsẹ, awon giga aromoni lati awon aromọ..
wikipedia
yo
Tálẹ́ńtì RaenJan jẹ́ sísọ, látọwọ́ ẹni pàtàkì olùṣemathiki ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì G.H.H..
wikipedia
yo
Hardy, pé ó wà nídúró kannã bí ti àwọn olùṣemathiki bi EUler, Gẹ̀tọ́nààn, Newton àti Archimedes .A bi ní èròdé, Tamil Nadu, India, Rmanu kọ́kọ́ pàdé Mathihiki Alágbese nígbà tó tó ọmọ ọdún 10..
wikipedia
yo
O fi ẹ̀bùn rẹ ori rẹ han, wọn sì fun ní àwọn ìwé Lori Trigonometry àgbéga ti s..
wikipedia
yo
Loney kò.Ìtọ́kasí Ọjọ́ìbí ni 1887àwọn Ojoaláìsí ní 1920àwọn ará India..
wikipedia
yo
Ajìyà Dmar Sen, Chch (, Oporto Kumar Shen; Ọjọ́ìbí 3 November 1933) jẹ́ ará India aṣe-okòwò tó gbà ní 1998 Ẹ̀bùn Nobel nínú àwọn sáyẹ́ńsì fún-okòwò fún ipa rẹ̀ sí ọ̀rọ̀-okòwò ìtọ́jú àwùjọ àti ìró àyánmú àwùjọ, àti fún ìjọlógún rẹ̀ sí àwọn ìṣòro àwọn tálákà àwùjọ..
wikipedia
yo
Sen Gbajúmọ̀ fún iṣẹ́ rẹ̀ lórí àwo Ohú tí ó únfà iyán, tó fa ìdàgbàsókè ojutu àmúlò wá láti dínà tàbí Kekuru àwọn ipa àìtọ́ onjẹ láwùjọ..
wikipedia
yo
ntnt ati ojogbon oro-okowo ati imoye ni Harvard University..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ẹlẹgbẹ́ àgbà ní Harvard Society of Fellows àti ẹlẹgbẹ́ Trinity College, Cambridge, níbi tó ti ṣiṣẹ́ tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀ bí ọ̀gá láti 1998 di 2004..
wikipedia
yo
Ohun olukọni ara Asia ati India akọkọ to jẹ olori kọlẹji oxbridge.Ìtọ́kasí ẹlẹ́bùn Nobel ninu ọrọ-oko-awon ẹlẹ́bùn Nobel ará India..
wikipedia
yo
Jean-Michel Basquiat (December 22, 1960 - August 12, 1988) jẹ́ oníṣọ̀nà ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Ó bẹ̀rẹ̀ bí oníṣọ̀nà grafiti ní New York City ní òpin ẹ̀wádún 1970, ó sì ṣe ní ẹ̀wádún 1980 àwòrán kíkún àlàfarahàn-tuntun..
wikipedia
yo
Basquiat kú nítorí ìlòkulò herose ní August 12, 1988, nígbà tó jẹ́ ọmọ ọdún 27.Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1960àwọn Ọjọ́aláìsí ní 1988àwọn ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Mary Anne (Mary Ann, Marian) Evans (22 November 1819 – 22 December 1880), daada pẹ̀lú orúkọ ìkọ̀wé rẹ̀ George Eliot, jẹ́ alakodun ara Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì, onílọ́we àti ayẹpadà, àti ìkan nínú àwọn olùkọ̀wé èaṣíwájú ìgbà ffik.[4..
wikipedia
yo
Ó ko akọ́dùn méjì, nínu wọn ní The Mill on the Floss (1860), Sislas Marner (1861) MiddleMarch (1871-72), àti Daniel Nyaranda (1876), ọ̀pọ̀ wọ́n dá lórí ìríkoko Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì, wọ́n sì gbájúmọ́ fún iṣẹ́Onigìdì àti Irù Waves wọn.Ìtọ́kasí Wọn Ọjọ́ìbí ní 1819 ní OAláìsíde ní Ara Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì..
wikipedia
yo
Àṣà ilẹ̀ Áfríkà pọ̀ lóríṣiríṣi , tí ó sì ní ìdàpọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ẹ̀yà ti ọ̀kọ̀ọ̀kan ní ìhùwàsí aláìlẹ́gbẹ́ wọn láti orílẹ̀ Áfíríkà ..
wikipedia
yo
O jẹ ẹsin àwọn oniruuru eniyan ti o ngbe ni orile Afirika ati àwọn ará ìlú Afirika ..
wikipedia
yo
Ní àkótán, àṣà ni àkójọpọ̀ àwọn agbára ìyàsọ́tọ̀ tí ó jẹ́ ti ẹgbẹ́ kan ti ènìyàn kan..
wikipedia
yo
Lára àwọn ànímọ́ wọ̀nyí ni àwọn òfin, ìwà rere, ìgbàgbọ́, ìmọ̀, iṣẹ́ ọ̀nà, àṣà, àti àwọn ànímọ́ mìíràn tí ó jẹ́ ti àwọn ènìyàn àwùjọ náà..
wikipedia
yo
Áfíríkà ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè ti ẹ̀yà gbogbo pẹ̀lú àwọn agbára oríṣiríṣi bíi èdè, àwọn àwòpọ̀, ìkíni àti àwọn ìjọ..
wikipedia
yo
Gbogbo àwọn ènìyàn Áfíríkà pín lẹ́sẹsẹ tí wọ́n sì ní àwọn àmì àṣà èyítí ó mú àṣà Áfíríkà yàtọ̀ sí ìyókù ní àgbáyé..
wikipedia
yo
Bí àpẹẹrẹ, àwọn ìṣesí àwùjọ, ẹ̀sìn, ìwà, àwọn ìṣèlú, ètò-ọrọ ajé, àti àwọn ìwúlò ẹwà gbogbo ṣẹ alabapin sí àṣà Áfíríkà..
wikipedia
yo
Àwọn ìlàkò àṣà pọ̀ lọ́pọ̀lọpọ̀ láàrin Áfíríkà, pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn onírúurú àṣà kìí ṣe ní àwọn orílẹ̀-èdè orírírí nìkan ṣùgbọ́n àwọn àwọn orílẹ̀-èdè kọkàn..
wikipedia
yo
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn àṣà ìbílẹ̀ Áfíríkà yàtọ̀ síra, síbẹ̀, nígbà tí wọ́n bá kẹ́kọ̀ọ́ jinlẹ̀ nípa rẹ̀, wọ́n rí i pé wọ́n ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àfiwé; fún àpẹẹrẹ, àwọn ìwà tí wọ́n wù, ìfẹ́ àti ìbọ̀wọ̀ wọn fún àṣà wọn, bákannáà owó tí ó lágbára tí wọn ń mú fún àwọn àgbàlagbà àti àwọn ẹni pàtàkì, bí àwọn ọba àti àwọn ìjòyè.Áfíríkà ti ní ipa ní orílẹ̀ yòókù, àwọn orílẹ̀ yòókù nã sì ti nípa lórí orílẹ̀ Áfíríkà..
wikipedia
yo
Eyi ni a le ṣe afihan ni ifarakanra lati ṣe deede si Agbaye ode oni ti n yipada nigbagbogbo dipo ki o duro fìdímúlẹ̀ ninu àṣà ilawe wọn.akopọ itan Afirika pin si ọpọlọpọ awọn aṣa ati ẹya..
wikipedia
yo
isọdọtun àṣà ti orílẹ̀ náà tún ti jẹ abala pàtàkì ti orílẹ̀-èdè lẹhin-òmìnira, pẹ̀lú idanimọ iwulo lati lọ awọn orisun aṣa ti Afirika lati jẹki ilana ti eto-ẹkọ, to nilo ẹda ti agbegbe ti o ni agbara ni ọpọlọpọ awọn ọna..
wikipedia
yo
Ni àsikò yi, ìpè fún Ìtọ́kasí ti ó tóbi púpọ̀ lori ìwọ̀n àṣà ni gbogbo àwọn ẹ̀yà ti idagbasoke ti di ohun tí ó pọ̀ si..
wikipedia
yo
Lakoko Ijọba Roman ti Ariwa Afirika (awọn apakan ti Algeria, Libya, Egypt, ati gbogbo Tunisia), awọn agbegbe bii TripoliTania di awọn olupilẹṣẹ ounjẹ fun olominira ati ijọba naa..
wikipedia
yo
Eyi ṣe ipilẹṣẹ ọ̀rọ̀ púpọ̀ ni àwọn aaye wọnyi fun ọdun 400 ti wọn fisin àwọn ariwa yi..
wikipedia
yo
àwọn ará Faransé gba ọmọ Áfíríkà gẹ́gẹ́ bí Faransé tí ènìyàn yẹn bá fi àṣà Áfíríkà wọn sílẹ̀ tí ó gba ọ̀nà àti ìṣẹ̀ṣe Faransé..Ìtàn àti ẹ̀sìn gẹ́gẹ́bí gbogbo àwọn àṣà ènìyàn, ìtàn-àkọọ́lẹ̀ Áfíríkà àti ẹ̀sìn dúró fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn àwùjọ tí àwọn oríṣiríṣi àṣà ní Áfíríkà..
wikipedia
yo
bíi gbogbo àwọn ọ̀làjú àti àṣà, àwọn àròsọ ìṣàn omi tí ń wà káàkiri ni àwọn ara oríṣiríṣi ẹ̀yà ti Áfíríkà..
wikipedia
yo
Ni Etiopia, àwọn Kristiẹniti ati Musulumi dá àwọn abala pataki aṣa ara Etiopia pẹlu awọn aṣa ìjẹmọ ati ilana..
wikipedia
yo
àwọn ìtàn-àkọọ́lẹ̀ tún kó ipa pàtàkì ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọ̀nà àwọn àṣà Áfíríkà..
wikipedia
yo
Àwọn ìtàn ṣe àfihàn ìdánimọ̀ àṣà , àti títọ́jú àwọn ìtàn ti Áfíríkà tí yóò ṣe ìrànlọ́wọ́ láti tọ́jú gbogbo àṣà..
wikipedia
yo
Ni Afirika,àwọn ẹgbẹ to ni Asa ṣẹda itan nipasẹ ati lati sọ itan awọn ara orilẹ na..
wikipedia
yo
Awọn ẹgbẹ oriṣiriṣi ni Afirika ni awọn aṣa tabi awọn ayẹyẹ ti o yatọ fun itan-akọọlẹ, eyiti o ṣẹda oye ti iṣe ti ẹgbẹ aṣa kan..
wikipedia
yo
Sí àwọn ará ìta tí ń gbọ́ ìtàn ẹ̀yà kan, o pèsè ìfòyemọ̀ àti ìjìnlẹ̀ òye sí àwọn ìgbàgbọ́, ojú ìwòye, àti àṣà agbègbè nã..
wikipedia
yo
Fun àwọn eniyan agbègbè na, o gbà wọ́n láàyè láti yíká ìyàsọ́tọ̀ ti ẹgbẹ́ wọn..
wikipedia
yo
Wọ́n ń fi ìfẹ́-ọkàn àti ìbẹ̀rù ènìyàn hàn, bí ìfẹ́, ìgbéyàwó, àti ikú..
wikipedia
yo
Awọn itan-akọọlẹ ni a tun rii bi ohun elo fun Eko ati ere idaraya..
wikipedia
yo
Ìtàn ń pèsè ọgbọ́n láti ní òye àwọn àkókò kan láti oríṣiríṣi àwọn ìwòye àti pé ó tún ṣe àfihàn pé gbogbo àwọn ìsọ̀rọ̀ àti àwọn àṣeyọrí wa wáyé ní gbogbo àṣà àti jákèjádò àwọn àkókò oríṣiríṣi ti ìtàn..
wikipedia
yo
wọ́n pèsè ọ̀nà fún àwọn ọmọdé láti lóyè ohun èlò àti agbègbè àwùjọ..
wikipedia
yo
Gbogbo ìtàn ni ó ní ọgbọ́n láti kọ́ ènìyàn, gẹ́gẹ́bí iṣẹ́-rere ṣe ma ń borí ibi..
wikipedia
yo
Ní ọ̀pọ̀ ìgbà, ohun kíkọ́ àkókò tí ìtàn yóò jẹ́ ẹranko tí ń sọ̀rọ̀, tàbí ohun tí kò ní ẹ̀dá yóò ṣẹlẹ̀ sí ìhùwàsí ènìyàn..
wikipedia
yo
Bótilẹ̀jẹ́pé àwọn ìtàn-àkọọ́lẹ̀ wà fún eré ìdárayá, wọ́n mú òye ti ohun-ini ati ìgbéga wá sí àwọn agbègbè ilẹ̀ Áfíríkà..
wikipedia
yo
Awọn itan-akọọlẹ ẹranko jẹ iṣsalaye diẹ sii si ere idaraya ṣugbọn tun ni awọn ihuwasi ati awọn ẹkọ si wọn..
wikipedia
yo
Awon itan eranko ni deede pin si awon itan ẹtan ati awon itan ajore..
wikipedia
yo
Nínú àwọn ìtàn ẹranko, ẹranko kan yóò nígbàgbogbo ní ìhùwàsí kannã tàbí ipá nínú ìtàn kọ̀ọ̀kan, nítorínáà àwọn olùgbọ́ kò ní láti ṣe àníyàn nípa ìsọdi..
wikipedia
yo
Àwọn ipa tí ó gbajúmọ̀ fún díẹ̀ nínú àwọn ẹranko ni àtẹ̀lé yìí; ehoro ní gbogbo ìgbà ní onítàn, oníwaye àti àrékérekè, nígbà tí ehoro máa ń tàn lùrí jẹ..
wikipedia
yo
Awọn itan-ojo-si-ojo jẹ awọn itan to se pataki julọ, lai se pẹlu awada, ti o ṣalaye igbesi aye ojoojumọ ati awọn ijakadi ti agbegbe Afirika kan..
wikipedia
yo
Awon itan wonyi maa n gba iyan, Àsálà lowo iku, ibalopọ, ati oran idile, ni lilo Fọọmu orin kan nigba ti won n so opin itan naa.Awon aṣọ gegebi awon iru orin ti afonifoji nile ati iwo ti Afirika, orin Ariwa Afirika ni asopọ ti o sunmọ pẹlu orin aarin ila-oorun ati lo awon ipo aladun ti o jọra ( Maqamat )..
wikipedia
yo
ó ní ibití ó pọ̀jù, láti orin ti Égíptì àtijọ́ sì Berber àti orin Tuareg ti àwọn alárinrin aginjù..
wikipedia
yo
Orin iṣẹ́ ọnà tí ẹkùn náà ní fún àwọn ọgọọgọrun ọdún tẹ̀lé ìlànà ìlànà orin ,‘Larubawa ati ará ìlú Andálu ..
wikipedia
yo
Orin Somali jẹ́ déédé mìírànutonic, ní lílo àwọn ìpolówó márún fún Octave ní ìdàkejì sí ìwọ̀n Heptatonic (àkọsílẹ̀ méje) gẹ́gẹ́bí ìwọ̀n pàtàkì ..
wikipedia
yo