cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
A lè ri iyọ̀ láti inú omi òkun tabi àwọn òkúta ilẹ̀.Àwọn ioní inú iyọ̀ bí klóríni ati sódìọmú, ṣe pàtàkì fún ìwàláàyè gbogbo ohun ẹ̀dá alààyè..
wikipedia
yo
Iyọ̀ ń kópa nínú àmójútó omi inú ara, bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé jíjẹ́ iyọ̀ jù lè fa àìlera fún ara, ó lè fa ẹ̀jẹ̀ ríru.Ìtọ́kasí iyọ̀ jíjẹàwọn àdàpọ̀ sódìọmú..
wikipedia
yo
jẹ́ àsíá Orílẹ̀-èdè Serbia Orílẹ̀-èdè Olómìniraìtọ́kasrbíà Orílẹ̀-èdè Olómìnira..
wikipedia
yo
Àsíá Ilẹ̀ Vojvodina jẹ́ àsíá Orílẹ̀-ìtọ́kasíVojvodina..
wikipedia
yo
Tenerife, to jẹ erekuṣu ti Spain, ni o tobijulọ ninu awọn erekusu kanari mejejẹ ni Okun Atlantiki lẹba eti odo Afrika..
wikipedia
yo
Tenerife ni tobi ni 2034.38 ìlọ́poméjì kilometer, ó sì ní iye àwọn ènìyàn tó jẹ́ 899,8..33..
wikipedia
yo
Ni aarin ti awọn erekusu ni awọn Teide oke oníná, àwon ga oke ni Spain.itọkasi awọn erekusu Kanari..
wikipedia
yo
Gran Kanaria (ni Gẹ̀ẹ́sì, "Grand (or Great) Canary") jẹ́ Erékùṣù kan ninu àwọn Erékùṣù Kanari.Ìtọ́kasí àwọn Erékùṣù Kanari..
wikipedia
yo
plazas De Soraníà ("places of Sovereakẹ́kọ̀ọ́ty"), tẹlẹ̀tẹlẹ̀ bi "Africa Septenruonal lákòókò (Spanish North Africa) tabi lasan bi "Africa Ẹnilẹ̀" (Spanish Africa) je agbegbe orile-ede Spain ni North Africa to ni Bode Mo Morocco, àyàfi awon ilu àdáwà ce ati Melilla.itọkasi Spéì[itọkasi..
wikipedia
yo
Orílẹ̀-èdè Olómìnira NaGorno-Karabakh (nknk) ( , or Artsakh Republic ( ) jẹ́ dé facto Orílẹ̀-èdè Olómìnira to bùdó sí agbègbè NaGorno-Karabakh (tàbí agbègbè artsakh) ní gúúsù Kakásusu.ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Okwẹ̀sìlie Nwodo (Okomo) (Ọjọ́ìbí 28 July, 1950 ni Nsukka, Nigeria) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ati Gómìnà ìpínlẹ̀ Enugu tẹ́lẹ̀ lati 1992 dé 1993.Ìtọ́kasí Gómìnà ìpínlẹ̀ Enugu..
wikipedia
yo
Ahman jẹ́ ọmọ ológun orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Lotifẹ̀yìntì àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ẹnúṣìkà tẹ́lẹ̀.Ìtọ́kasí àwọn Gómìnà ìpínlẹ̀ Enugu..
wikipedia
yo
Benson Adewunmi Agbaje jẹ ọmọ ologun orile-ede Naijiria ati gomina Ipinle Enugu tẹlẹ.itọkasi awọn gomina ipinle Enugu..
wikipedia
yo
Chimaròkè ńnàmani (ojoibi May 1960) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Gómìnà ìpínlẹ̀ Ẹnúgu tẹ́lẹ̀.Ìtọ́kasí àwọn Gómìnà ìpínlẹ̀ Enugu..
wikipedia
yo
Kenneth ugh ńnà gbmani jẹ́ alàgbà aṣòfin ilẹ̀ Nigeria tẹ́lẹ̀ tó ṣojú fún ìpínlẹ̀ Enugu lati 2003 dé 2007..
wikipedia
yo
Ọmọ ẹgbẹ́ olóṣèlú People’s Democratic Party (PDP) jẹ́ùn..
wikipedia
yo
Ni 2005 o di Aare ile Alàgbà Asofin Naijiria titi di 2007.Ìtọ́kasí ara Naijiria..
wikipedia
yo
Gwendolyn Elizabeth Brooks (June 7, 1917 – December 3, 2000) jẹ́ Olùkọ̀wé ọmọ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Wọ́n yan bí poet Laureate ground in Poetry to the Library of Congress in 1985.Ìgbésí EweGwenlimú Elizabeth Brooks jẹ́ bíbí ní June 7, 1917, ní tóPékà, Kansas fún David Anderson Brooks àti Keziah Wms, ó jẹ́ àkọ́bí..
wikipedia
yo
Ìyá rẹ̀ jẹ́ olùkọ́ tẹ́lẹ̀ kí ó tó fi ṣe sílẹ̀ láti ṣètọ́jú àwọn ọmọ rẹ̀, baba rẹ̀, tó jẹ́ ọmọ ẹrú tó jà nínú ogun abẹ́lé, jẹ́ aṣọ́nà nítorípé kò ní ọwọ́ láti lósì ilé-ẹ̀kọ́ oníṣègùn láti di dókítà..
wikipedia
yo
Nigbati Brooks di ọmọ ọ̀sẹ̀ mẹ́fà, wọn ko lọ si Chicago, Illinois, nibi tó ti dàgbà.Ìtọ́kasí Ọjọ́ìbí ní 1917àwọn Ọjọ́aláìsí ní 2000àwọn Olùkọ̀wé Ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Ewì jẹ́ ìlò èdè lọ́nà àrà tí akéwì ń lò láti ṣàlàyé ọ̀rọ̀ tàbí gbé èrò ọ̀kan rẹ̀ jáde lọ́nà tó yàtọ̀ sí ọ̀rọ̀ geere..
wikipedia
yo
Akéwì ni Yorùbá máa ń pè ẹni tí ó ń kéwì.Oríṣi ewì YorùbáYorùbá ní oríṣi ewì méjì; ewì alohùn (oral Poetry) àti ewì àpilẹ̀kọ (written Poetry)..
wikipedia
yo
Ewì alohùn ni àwọn ewì àjogúnbá láti ọwọ́ àwọn baba ńlá wá..
wikipedia
yo
ohun ẹnu, nígbà mìíràn pẹlu ìlú, agogo ni a fi ń gbé e kalẹ̀..
wikipedia
yo
Bí àpẹẹrẹ; ìjálá, oríkì, ESA egúngún, Ẹkùn ìyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
ewì àpilẹ̀kọ ni àwọn ewì tí a fi ọgbọ́n àtinúdá gbé kalẹ̀ fún kíkà, yálà ní ilé-ẹ̀kọ́ tàbí fún ara ẹni..
wikipedia
yo
Ewì àpilẹ̀kọ lọ́pọ̀ ìgbà ló ma ń yí padà sí alohùn pàá pàá jùlọ ní ayé òde òní tí ìmọ̀ mọ̀ọ́kọ mọ̀ọ́ká ti gbòde kan kan.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
mpeta-3 jẹ́ ìtọ́kasí fún àwọn àdìpọ̀ ọ̀págun iṣẹ́ àmìọ̀rọ̀ ọ̀hún àti fíú ti Moving Picture Experts ( (mpe) pinnu lé láti lò fún àwọn àmì HdTV ní 1080p ní ãrín 20 sí 40 mega MEA Second.Ìtọ́kasí WUNIG Official Official pèG G’’
wikipedia
yo
Moving Picture Experts Group (mpe) jẹ́ ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ àwọn olóyè tí ó jẹ́ dídásílẹ̀ látọwọ́ ìṣọ́ láti ṣákojọpọ àwọn ọ̀págun fun Ìpamọ́papọ̀ olóhùn àti fípapọ̀ àti Irankiri wọn..
wikipedia
yo
O je didasile ni 1988, wo se ipade akọkọ wọn ni May 1988 ni Ottawa, Canada.itọkasi..
wikipedia
yo
Nínú ìmọ̀ kọ̀mpútà, Jgg (, ) (orukọ fun Joint Photographic Experts Group, to ṣẹda ọ̀págun na) jẹ́ ọnà tó wọ́pọ̀ tó n jẹ́ lilo fun Ìgẹ̀kúrú Aṣọnu fun awọn aworan fọto. Aroko ìsọ..
wikipedia
yo
Thomas Hobbes (5 April 1588 - 4 December 1679), nínú àwọn ìwé ijọ́un miran bí Thomas Hobbs ará Malmsbury, jẹ́ ara Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì tó jẹ́ onímọ̀ oyè, tí a mọ̀ loni fún iṣẹ́ rẹ̀ lórí ìmọ̀-oyè olóṣèlú..
wikipedia
yo
Ìwé rẹ̀ ọdún 1651 Leviwálé Ṣẹ̀dásílẹ̀ ipilẹṣẹ fún ọ̀pọ̀ ìmọ̀-òye olóṣèlú iwoorun láti ẹgbẹ́ Èrò Májẹ̀mú Àwùjọ.Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1588àwọn Ọjọ́aláìsí ní 1679àwọn ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì..
wikipedia
yo
Lọ́pọ̀ BC) Ryls jẹ́ Gkọ́lọ́fín olùkọ́ìtàn àti Olùkọ̀wé Ìtàn Ogun àwọn ará ìṣàpẹẹrẹen, tó sọ nípa ogun ọ̀rúndún 5 K lãrín Spárs àti Athens títí dé ọdún 411 Kj..
wikipedia
yo
Thuskys jẹ́ mímọ̀ bí baba "ìtàn òní nítorí àwọn ọ̀nà tó lò láti ṣàkójọ ìdí àti ìgbẹ́yẹ̀wò nípa ítorí àti Ifá láì mẹ́nu mẹ́nu ba ipa àwọn Ọlọ́run, gẹ́gẹ́ bó ṣe jẹ́ ẹyìnsílẹ̀ nínú ìbẹ̀rẹ̀ sí iṣẹ́ rẹ̀.Wọ́n tún pè bí baba-ẹ̀kọ́ Àjọ̀dún-Ẹ̀kọ́ṣì olóṣèlú, tó ń fojúwo àwọn ìbáṣepọ̀ lãrín àwọn orílẹ̀-èdè pé wọ́n dá lórí agbára kúkú ẹ̀tọ́.Ìtọ́kasí ìgbésíayé..
wikipedia
yo
Sunday Ajibade Adenihùn jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti gómìnà ìpínlẹ̀ Imo tẹ́lẹ̀.Ìtọ́kasí sígómìnà ìpínlẹ̀ Imo..
wikipedia
yo
Samuel onunaka Mbakwe (1929 - 2004) jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti gómìnà ìpínlẹ̀ ìmọ̀ tẹ́lẹ̀.Ìtọ́kasí gómìnà ìpínlẹ̀ ìmọ̀..
wikipedia
yo
Ike Omar Sanda Nwachukwu (Ọjọ́ìbí September 1, 1940) jẹ́ ọmọ ológun Titifẹ̀yìntì àti olóṣèlú ará ilẹ̀ Nàìjíríà tó di ọ̀pọ̀lọpọ̀ mú ní ìjọbaNàìjíríà, ó di alákóso ọ̀rọ̀ òkèrè lẹ́ẹ̀mejì, Gómìnà ìpínlẹ̀ ìmọ̀ àti alàgbà nínú àwọn aṣojú ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin lati Ìpínlẹ̀ Ábíá. Àwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ìpínlẹ̀ ìmọ̀ ilẹ̀ alàgbà iṣẹ́ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Jaja Aanu Waschuku (1 January 1918 - 7 November 1996) jẹ oloselu ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà.Ìtọ́kasí ara Naijiria..
wikipedia
yo
Akinwándé Bọlaji akínyẹmí tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrin oṣù kìíní ọdún 1942 (January 4, 1942) jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n Onímọ̀ sáyẹ́ńsì, olólúlúlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tó di Alákòso ọ̀rọ̀ òkèrè Nàijíríà láti 1985 títí dé òpin 1987..
wikipedia
yo
Ohun ni Alaga National think tank.Awon itọkasi awon ara Naijiria..
wikipedia
yo
Onike Guy ikweche (25 February 1951 - 10 November 2009) je omo ologun oju-omi orile-ede Naijiria to je yiyan si ipo Gomina ipinle imo lati 1986 de 1989 nigba ijoba ologun Ọ̀gágun Ibrahim Babangida.Ìtọ́kasí Gomina Ipinle Imo..
wikipedia
yo
Ogubaà jẹ́ ọmọ ológun orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ati gomina ìpínlẹ̀ Imo tẹ́lẹ̀.Ìtọ́kasí gomina ìpínlẹ̀ Imo..
wikipedia
yo
Aneke jẹ́ ọmọ Ológun orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Gómìnà ìpínlẹ̀ Imo tẹ́lẹ̀.Ìtọ́kasí àwọn Gómìnà ìpínlẹ̀ Imo..
wikipedia
yo
tànko Zubairu jẹ ọmọ ologun orile-ede Naijiria ati gomina Ipinle Imo tẹlẹ.Ìtọ́kasí awọn Gomina Ipinle Imo..
wikipedia
yo
Achike Udenwa je omo ologun orile-ede Naijiria ati gomina Ipinle Imo tele.Ìtọ́kasí Gomina Ipinle Imo..
wikipedia
yo
Garba Ali Mohammed jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti gómìnà ìpínlẹ̀ Niger tẹ́lẹ̀.Ìtọ́kasí Ọjọ́ìbí ní 1949àwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ Niger..
wikipedia
yo
Kwan GWadada je omo ile Naijiria ati gomina ipinle Niger tele.Ìtọ́kasí Gomina ipinle Niger..
wikipedia
yo
Musa inuwa (1948 - 16 January 2010) je omo ile Naijiria ati gomina ipinle Niger tele.Awon Ọjọ́ìbí ni 1948awon ojoAláìsí ni 2010awon Gomina ipinle Niger..
wikipedia
yo
Cletus kòmena Emein jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti gómìnà ìpínlẹ̀ Niger tẹ́lẹ̀.Ìtọ́kasí Gómìnà ìpínlẹ̀ Niger..
wikipedia
yo
Abdulìkórèr dari je omo ile Naijiria ati gomina ipinle Niger tele.Awon gomina ipinle Niger..
wikipedia
yo
Jẹ́ alàgbà ní Ilé Alàgbà Aṣòfin Nàìjíríà láti 1999 dé 2003.Ìtọ́kasíàwọn olóṣèlú ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
David Cobhaà Brigìdì jẹ́ amòfin àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú àárín Balyé ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O jẹ aṣoju ni ile igbimo asofin leyin ti o wole latari eto idibo ti osu kerin odun 1999 labẹ egbe oselu People's Democratic Party.Awon itọkasiàwọn oloselu ara Naijiriaka kukuru..
wikipedia
yo
(1948-2022) jẹ́ alàgbà ní ilé alàgbà aṣòfin Nàìjíríà láti 1999 dé 2003.Ìtọ́kasíàwọn olóṣèlú ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
PeruPH Lokarieweh Wabara je alagba ni ile alagba asofin Naijiria lati 1999 de 2003.Awon oloselu ara Naijiria..
wikipedia
yo
Daniel Olúgbénga Àlùkò (ọjọ́ 20 July, 1963 – 20 November, 2021) jẹ́ alàgbà ní ilé alàgbà aṣòfin Nàìjíríà láti 1999 dé 2003.Àwọn olóṣèlú ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Jẹ́ alàgbà ní ilé alàgbà aṣòfin Nàìjíríà láti 1999 dé 2003..
wikipedia
yo
O ṣoju fun iwoorun Enugu lati ẹgbẹ oloselu appitọ́kasíàwọn oloselu ara Naijiria..
wikipedia
yo
Idris Abubakar (1957 – 10 December, 2002) jẹ́ alàgbà ní ilé alàgbà aṣòfin Nàìjíríà láti 1999 dé 2003.Ìtọ́kasíàwọn olóṣèlú ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
(1938-2022) jẹ alàgbà ni ilẹ̀ alàgbà aṣòfin Nàìjíríà lati 1999 dé 2003.Ìtọ́kasíàwọn olóṣèlú ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
jẹ́ alàgbà ní ilé alàgbà aṣòfin Nàìjíríà láti 1999 dé 2003.Ìtọ́kasí àwọn olóṣèlú ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Jẹ́ alàgbà ní Ilé Alàgbà Aṣòfin Nàìjíríà lati 1999 dé 2003.Ìtọ́kasíàwọn olóṣèlú ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
jẹ́ àgbà ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà Nàìjíríà]] láti 1999 dé 2003.Ìtọ́kasíàwọn olólúlú ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
(1933-2021) jẹ́ alàgbà ní ilé alàgbà aṣòfin Nàìjíríà lati 1999 dé 2003.Ìtọ́kasíàwọn olóṣèlú ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
(1930-2019) jẹ́ olóṣèlú àti ọmọ ilé aṣòfin àgbà Nàìjíríà nígbà kan rí láti ọdún 1999 sí ọdún 2003 tí ó sojú ìlà oòrùn ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú Alliance for Democracy (AD)..
wikipedia
yo
Wọ́n yàn án sínú ìgbìmọ̀ tí ó ń ṣe àṣàyàn.Ìgbésí ayé rẹni oṣù kejìlá ọdún 2003, Alhaji Ahmed Abdulunr, tí ó jẹ́ Alága gbọ́ggbogbo fún ẹgbẹ́ òṣèlú Alliance for Democracy tí ó ń fipò sílẹ̀ kọ̀wé sí Àjọ elétò ìdìbò (INEC), láti fi ẹsẹ̀ Akinfẹ́nwa rinlẹ̀ gẹ́gẹ́ bí alága gbogbo gbọ́ tuntun fún ẹgbẹ́ òṣèlú náà náà..
wikipedia
yo
Ẹgbẹ́ òṣèlú yí ti pín tẹ́lẹ̀ sí ọ̀nà méjì , tí Olóyè Bísí Adésí jẹ́ adarí fún apá kejì..
wikipedia
yo
Fundi eyi, ninu osu keji odun 2004, ajo INEC pe ipade awon olori olori ninu egbe naa yato si awon adari mejeji yi, lati ba won pana tii to wa ninu egbe naa amo ti ìpètù ṣaáwọ̀ naa si forí ṣánpọ́n..
wikipedia
yo
Ẹgbẹ́ Afẹ́nifẹ́re sì fi ìfẹ́ẹ̀ wọn hàn sí Akinfenwa láti di alága gbogbo gbọ́ fún ẹgbẹ́ náà..
wikipedia
yo
Akinfenwa fese re mu ni osu keji odun 2006 wipe oun ni iwo gbo fun egbe oselu Alliance for Democracy ni ile Naijiria, wipe kii se Oloye Bisi ori oloselu.Awon oloselu ara Naijiria..
wikipedia
yo
Adebayo Salami ti oruko inagijẹ re n je oga Bello (ti won bi ni ojo-an osu karun-un odun1953 odun 1953) je gbajumo osere oludari ati olóòtú sinima àgbéléwò ọmọ Ìpínlẹ̀ Kwara lórílẹ̀-ede Naijiria.Awon Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Jẹ́ alàgbà ní ilé alàgbà aṣòfin Nàìjíríà láti 1999 dé 2003.Ìtọ́kasíàwọn alàgbà aṣòfin Nàìjíríà láti ìpínlẹ̀ Oyoàwọn olóṣèlú ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
jẹ́ Aṣojú-ṣòfin ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin orílẹ̀èdè Nàìjíríà lọ́dún 1999 sí ọdún 2003..
wikipedia
yo
Tokunbo afikútúmọ̀ jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀èdè Nàìjíríà, tí ó ti fi ìgbà kan rí jẹ́ ṣenétọ̀ tí ó ń ṣojú ẹkún gbùngbùn ẹ̀kọ́ ní ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ìjọba Olómìnira ìkẹrin lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú AD (Alliance for Democracy)..
wikipedia
yo
Ó gbáwọ́ ẹkùn ní Oṣù Igbe ní ọdún 2002 kúrò ní gbùngbùn lọ sí apá àríwá, lẹ́yìn tí Sẹ́néto Wahab Dosunmu sídìí lọ sí ẹgbẹ́ òṣèlú PDP.ìtàn ìgbésí ayépọ̀̀jì ara Nàíjíríà ara Nàíyàn..
wikipedia
yo
Aṣèṣe ọlábímtán (11 June, 1932 – 27 August, 2003) jẹ́ alàgbà ní ilé alàgbà aṣòfin Nàìjíríà láti 1999 dé 2003.Àwọn Ọjọ́ìbí ní 1932Àwọn Ọjọ́aláìsí ní 2003àwọn olóṣèlú ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Uche Chukwumerije (osu Kọkànlá odun 1939 si ojo ọkàndínlógún osu kerin odun 2015) je oloselu omo orile ede Naijiria ti won dibo yan wole gege bi asoju Ariwa Abia, Ipinle Abia ni ile igbimo asofin agba ti ile Naijiria..
wikipedia
yo
O je asoju ni ile igbimo asofin lati osu kerin odun 2011 si osu kejila odun 2015 labe egbe oselu People People’s Democratic Party.Awon itọkasiawon oloselu ara Naijiri Ọjọ́ìbí ni 1939..
wikipedia
yo
Jẹ́ alàgbà ní ilé alàgbà aṣòfin Nàìjíríà láti 2003 dé 2007.Ìtọ́kasíàwọn olólúlú ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ike Ekwereẹgbẹ̀rún jẹ́ olóṣèlú ará Nàìjíríà àti alàgbà ní ilé alàgbà aṣòfin Nàìjíríà láti 2003 títí di oṣù karùn-ún ọdún 2023..
wikipedia
yo
Ni 2007 o di Igbakeji Aare ile Alàgbà Asofin si David Mark..
wikipedia
yo
Ni 23 Okudu 2022, a fi ẹsun kan Ekweretàbí pẹlu iyawo rẹ ni ile-ẹjọ sísuns— ilu UK pẹlu Igbimọ lati ṣeto irin-ajo ti ọmọ ọdun 21 kan si UK lati le ikore awọn ẹya ara.Awon itọkasiàwọn oloselu ara Naijiria..
wikipedia
yo
jẹ́ àgbà olóṣèlú ọmọ bíbí ìlú Èkó nílẹ̀ Yorùbá lápá gúsù ìwọ̀-oòrùn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O ti fìgbà kan jẹ́ aṣòfin-àgbà (Senator) ní ọdún 2003 sí 2007 níbití ó ti sojú ìpínlẹ̀ èkó nílé ìgbìmọ̀ aṣòfin-àgbà..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2014, Aare-ana, Goodluck Jonathan yan-an gẹgẹbi Minister-kéréje fun aabo orile-ede (BOUnse Minister of State).Àwọn Ìtọ́kasíàwọn oloselu ará Naijiria..
wikipedia
yo
Adéwá Olúwáì lámọ́ tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìndíndì Oṣù Kejì ọdún 1953 (16 February 1953) jẹ́ gbajúmọ̀ olóṣèlú àti Mínísítà kékeré fún ètò ìlera lọ́wọ́lọ́wọ́ lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó ti fi ìgbà kan jẹ́ agbẹnusọ Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin ti Ìpínlẹ̀ Èkó lọ́dún 1999, bẹ́ẹ̀ náà wọ́n dìbò yàn án gẹ́gẹ́ bí Sẹ́nétọ̀ lọ́dún 2007, láti ṣojú lábẹ́ ásìya ẹgbẹ́ òṣèlú Action Congress..
wikipedia
yo
in 2003 he was appointed chairman of the Senate Committee on Ethics, Èèyàncare and Public Uìdionsàwọn ìtọ́kasíàwọn olóṣèlú ara Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ọjọ́ karùndílọ́gbọ̀n oṣù ṣeré ọdún 1958 ni wọ́n bí ọ̀kan lára àwọn olóṣèlú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó ti fi ìgbà kan jẹ́ gómìnà ìpínlẹ̀ Ògùn rí, Ibikunle àmọ̀sùn, bẹ́ẹ̀ náà ni ó jẹ́ sẹ́líto orílẹ̀-èdè Nigeria rí lẹ́ẹ̀mejì..
wikipedia
yo
Oṣu Igbe 2003 si Oṣu Igbe 2007 ni Ibikunle fi jẹ Senétọ̀ fun agbeagbe arin gbúgbú ipinlẹ Ogun, Orilẹ-ede Naijiria..
wikipedia
yo
Ó di gómìnà ní ìpínlẹ̀ Ògùn lábẹ́ àsíá ẹgbẹ́ ACN ní ọdún 2011 lẹ́yìn tí ó fìdí rẹmi ní ìgbà àkọ́kọ́ tó díje dupò..
wikipedia
yo
O dije dupo fun ipo gomina fun saa keji ni abẹ ẹgbẹ oṣelu APC, leyin ti o wole, won se ìbúra fun un ni ojo kankandilogbo osu Èbìbì odun 2015.Awon itọkasi awon gomina ipinle ogunàwọn oloselu ara Naijiria..
wikipedia
yo
Teslim Folarin (Ọjọ́ìbí October 1963) jẹ́ alàgbà ní ilé alàgbà aṣòfin Nàìjíríà láti 2003 dé 2007.Ẹ̀sùn Iṣẹ́kúpa 4 January, 2011 ọlọ́ọ̀pá Nàìjíríà fẹ̀sùn kan Folarin àti àwọn mẹ́ta míràn, Owole Gobaoba, Baltimore Raji àti ràímì àti wọ́n lọ́wọ́ nínú ikú nínú ikú gbogbo jẹ́ Olórí ẹgbẹ́ kan Nu KanrtwW Ẹ̀ka Ìpínlẹ̀ Oyo.Ní 13 January Nàìjíríà, ọlọ́ọ̀pá Nàìjíríà fagile ti wọ́n fi kan fi kan bí Èkó-ẹjọ́ ní Ibadan tu sílé kúrò tó alàgbà aṣòfin lati Ìpínlẹ̀ Nàìjíríà láti Ìpínlẹ̀ Ara Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Jẹ́ alàgbà ní ilé alàgbà aṣòfin Nàìjíríà láti 2003 dé 2007.Ìtọ́kasí alàgbà aṣòfin Nàìjíríà láti ìpínlẹ̀ Oyoàwọn olóṣèlú ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Isiaka Abiola Ajimobi (ojoibi 16 December 1949-2020) je oloselu omo orile-ede Naijiriaati gomina ipinle Oyolati 29 osu karun 2011 titi di 2019..
wikipedia
yo
O tun jẹ Alàgbà ni Ile Alàgbà Asofin Naijiria lati 2003 de 2007.itọkasi awọn Gomina ipinle Oyoawon alàgbà asofin Naijirialati ipinleOyo Oyoawon oloselu araNaijiria..
wikipedia
yo
Jẹ́ alàgbà ní ilé alàgbà aṣòfin Nàìjíríà láti 2003 dé 2007.Ìtọ́kasíàwọn olóṣèlú ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Badamasi Maccido (1961-2006) jẹ́ alàgbà ni ilé alàgbà aṣòfin Nàìjíríà láti 2003 dé 2006 nígbà tó kú nínú Iìjàǹbá Baata Adc Airlines Flight 53 pẹ̀lú bàbá rẹ̀ Moṣèèṣì Maccido àti ọmọ rẹ̀.Ìtọ́kasí Ọjọ́ìbí ní 1961àwọn Ọjọ́lọ́lọ́ ní 2006àwọn olóṣèlú ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo