cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
A bí Aliyu magatakarda Wamakko ni ojo kinni, osu keta, odun 1953..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2007, nínú oṣù kẹẹ̀rin wọn dìbò yán-án sí ipò gómìnà ìpínlẹ̀ ṣòkòtò, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, lẹ́ni tó ń ṣe aṣojú ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party, (PDP)..
wikipedia
yo
Ẹgbẹ́ yìí ni a mọ̀ sí ẹgbẹ́ oní “Um".eto-ẹkọ àti ìṣe rẹ̀ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ àwọn Olùkọ́ni tí a mọ̀ sí Teachers’ College, nílùú Sokoto, láàrín ọdún 1968 sí ọdún 1972, léyìí tó lo ọdún márùn ún gbáko..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tó parí ẹ̀kọ́ rẹ̀, ó ṣiṣẹ́ olùkọ́ni láàrín ọdún 1973 sí 1977, kó tó wá lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga fásitì, Univercity of Pittsburgh ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Ó padà sí ilẹ̀ Nàìjíríà, ó ṣiṣẹ́ èkó nílé ẹ̀kọ́ Olùkọ́ni, ìyẹn Teachers’ College.Puv,ko, ṣiṣẹ́ ní Ilé-iṣẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ Zumi mi gẹ́gẹ́ bíi igbákejì Akọ̀wé..
wikipedia
yo
Wọ́n gbéga lẹ́nu iṣẹ́ rẹ̀ lọ sípò adelé akọ̀wé..
wikipedia
yo
Wọ́n yàn sípò alága ìjọba ìbílẹ̀ ṣòkòtò, láti ọdún 1986 sí ọdún 1987.makmakko di ọ̀gá pátápátá ilé iṣẹ́ ibi ìgbafẹ́ fáwọn arìnrìn-àjò àti ilé ìtura, ní ṣòkòtò..
wikipedia
yo
Ni odun 1992, osu keta, Wamakko ni igbega si ipo oludari agba fun awon akanse ise, ni ofiisi Gomina, ni Ipinle Sokoto.eto iselu rẹni odun 1999, Wamakko di Igbakeji Gomina Attahiru Bafarawa ti Ipinle Sokoto ninu egbe oselu, All Nigeria Peoples' Party (ANPP)..
wikipedia
yo
Ẹ̀wẹ̀, àwọn ará ìlú dìbò yàn-án lélẹ̀ kejì sípò igbákejì gómìnà, ní oṣù kẹrin, ọdún 2003..
wikipedia
yo
Ó kọ̀wé fipò igbákejì gómìnà sílẹ̀ ní ọjọ́ kẹ́ẹ̀dógún, oṣù kẹta, ọdún 2006.Nínú oṣù kẹrin, ọdún 2007, ni Wámakkọ díje fún ipò gómìnà ìpínlẹ̀ ṣòkòtò lábẹ́ àsíá People’s Democratic Party, ó sì jáwé olúborí..
wikipedia
yo
Ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n, oṣù kaàrún, ọdún 2007, ni gómìnà wamakko bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi gómìnà .Amo sa, ní oṣù Kẹẹ̀rin, Ọdún 2008, ní ìwé ìpẹ̀jọ́ dé, tí wọ́n sì fagile Èsì ìdìbò gómìnà Wamakko nítorí wípé, ó wà nínú ẹgbẹ́ All Nigeria Peoples Party, (ANPPPP), nígbà tí ó lọ díje dupò gómìnà, tó sì pegedé lórí ẹgbẹ́ Asia People’s Democratic Party, (PDP)..
wikipedia
yo
Ilé-ẹjọ́ pàṣẹ pé ki Abdullahi Blaralara Salame, bọ̀ sípò adelé Gómìnà, láti ọjọ́ kọkànlá, Oṣù Kẹẹ̀rin, sí ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n, Oṣù Kaàrún, Ọdún 2008, (11 April – 28 May 2008), tí àwọn elétò ìdìbò fi tún ètò ìdìbò míràn ṣe..
wikipedia
yo
Ètò ìdìbò laarin Wamakko àti Muhammadu Maigari dingyadi tó díje láti ẹgbẹ́ Dpp, pẹ̀lú Wamakko àti Attahiru Báfarawa, tó jẹ́ olùdásílẹ̀ ẹgbẹ́ Òṣèlú DPP..
wikipedia
yo
Wamakkọ tún jáwé olúborí lélẹ̀kejì, sípò gómìnà ó sì bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ìlú nínú oṣù kaàrún ọdún 2008..
wikipedia
yo
Oludije elegbe rẹ wa so wipe oun yoo tun gbálẹ̀ ejo lo lati lo tako EberemigòMgoclusimi.Ni odun 2007, Wamakko se ifilọlẹ eto lẹ́sẹ̀ẹ́wọ̀gbẹ́ ti a mo si State Poverty Inru Agency, (Sijoba), lati pese ise fawon Odo..
wikipedia
yo
Ninu oṣù lásán, ọdún 2009, ó tún ṣe ìpèsè ilé gbígbé bíi ẹgbẹẹ̀rún meji fáwọn ará ìlú..
wikipedia
yo
Síwájú síi, ó ṣàlàyé wípé òun kò ní dá ilé ìfowópamọ́ sílẹ̀, ṣùgbọ́n ìjọba òun yóò ṣàtìlẹyìn fún ẹnikẹ́ni tó bá nífẹ̀ẹ́ síi..
wikipedia
yo
Ní Oṣù Kẹẹ̀wá, Ọdún 2009, Komisona fún ètò Ìgbẹ́jọ́ ní Ìpínlẹ̀ sọ wípé Wọ́n ṣetán láti ṣe Kiwadi Gómìnà, tẹ́lẹ̀rí Attahiru Bfarawa àti àwọn marun míràn fún ìwà àjẹbánu àti iṣẹ́-ọwọ́ ìlú tó tó bilionu mẹta naira (n2.919 Billion), Mokú-Mokú nígbà tí ó wà lórí ipò gómìnà..
wikipedia
yo
Báfarawa pe akiyesi àwọn àjọ Olúwaádi tí gómìnà Wamakko ti Ipinle Sokoto, pe wọn fese atako oun ati ise ti oun se, nigba ti oun wa lori aga ori gomina tele o sọ siwaju sii,ko ni igbakeji oun oun, nigba ti oun je gomina, o gba igbimo orile laarin won ranse si wa ki eto màá to to le bere..
wikipedia
yo
Àwon Olúwaádi wòye pé ọ̀rọ̀ náà ti di ìtì ọ̀gẹ̀dẹ̀ tí kò ṣe fọwọ́ bù.Àwọn ìtọ́ka síàwọn ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
This is a list of administrators and governors of Benue state..
wikipedia
yo
Benue state was formed on 1976-02-03 when Benue-Plateau state was Divided into Benue and Plateau States.Ẹ tún woàwọn ìpínlẹ̀ Nàìjíríàlist of all Nigerian state governorsReferencesBenueGomina..
wikipedia
yo
This is a list of administrators and governors of Plateau state.Plateau state, Nigeria was formed on 1976-02-03 when Benue-Plateau state was Divided into Benue state and Plateau State.Ẹ tun woawon ipinle Nàìjíríàlist of all Nigerian state governorsReferences 4..
wikipedia
yo
This is a list of administrators and governors of Sokoto state, Nigeria, which was formed on 3 February 1976 when north-western state was split into Niger and Sokoto states.Ẹ tún wọàwọn ìpínlẹ̀ Nàìjíríàlist of all Nigerian state GovernorSexìlànà Sọ́ọ̀lùínì Sokoto state governmenttémi gómìnà..
wikipedia
yo
This is a list of family of the Abuja Federal Capital territory.The Federal Capital territory, Abuja, Nigeria was formed in 1976 from parts of former Nasarawa, Niger, and kogi States.Ẹ tun woFederal Capital territory AdministrationStates of Nigerialist of all Nigerian state Governorṣàwọn itọka siagbegbe oluilu apapo..
wikipedia
yo
This is a list of administrators and governors of Akwa Ibom State.Akwa Ibom state was formed in 1987 when it was split from cross River state.Ẹ tun woStates of Nigerialist of all Nigerian state governorsreferencesakwa IbomGómìnà..
wikipedia
yo
This is a list of administrators and governors of Anambra State..
wikipedia
yo
Anambra State, Nigeria was formed on 3 February 1976 when east-Central state was Divided into Anambra and Imo (Owerri) Statese tun woStates of Nigerialistlist of Nigerian State governorsreferencesanambraGómìnà..
wikipedia
yo
AjoBena je omo orile-ede Naijiria ati Gomina Ipinle Abia tele.Awon Gomina Ipinle Abia..
wikipedia
yo
Tèmi ejòOr jẹ́ ajagunfẹ̀yìntì ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O ti fìgbà kan jẹ́ Gómìnà ìpínlẹ̀ Ábíá ati Enugu tẹ́lẹ̀ ri.Ìtọ́kasí awọn gomina ipinlẹ Abiawọn Gomina Ipinle Enugu..
wikipedia
yo
Anthony Obi (1952-2022) je omo orile-ede Naijiria ati Gomina Ipinle Abia tele.Ìtọ́kasíàwọn Gomina Ipinle Abia..
wikipedia
yo
Orji Uzor Kalu (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlélógún Oṣù Kẹrin ọdún 1960) jẹ́ olóṣèlú ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Ábíá lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Sáà Méjì Ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ Ló Lò gẹ́gẹ́ bí Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ábíá..
wikipedia
yo
Lọ́dún 2019, ó díje dupò sineto lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress, ó sìn wọlé..
wikipedia
yo
LỌ́JỌ́ karun-un osu kejila odun 2019, ile ejo da a lebi esun jìtì owo ti ijoba apapo fi kan an, won si fi i sẹ́wọ̀n odun mejila gbako.Awon itọkasiawon Gomina ipinle Abia..
wikipedia
yo
Jonathan Tunde Ojiji je Ọ̀gágun nibi ise ologun ile Naijiria to tifẹyìntì lati Ipinle kogi, O je Olùmọmójútó/Gomina ologun fun Ipinle Akwa Ibom ati leyin re fun Ipinle Bendel nigba ijoba ologun Ọ̀gágun Ibrahim Babangida (1985-1993)..
wikipedia
yo
Leyin ti oselu pada ni 1999 O je Yoriyan gege bi ayewo fun iwoorun kogi ni ile-igbimọ asofin Naijiria lati May 1999 titi di May 2007.Awon Gomina ipinle Akwa Ibom..
wikipedia
yo
je ara orile-ede Naijiria ati gomina ipinle Akwa Ibom tele.Awon gomina ipinle Akwa Ibom..
wikipedia
yo
Victor Bassey Attah (Ọjọ́ìbí 20 November 1938) jẹ́ ara orílẹ̀-èdè Nàìjíríààti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom tẹ́lẹ̀.Àwọn Ọjọ́ìbí ní 1938 Ìpínlẹ̀ Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom Ibom
wikipedia
yo
je ara orile-ede Naijiria ati gomina ipinle Akwa Ibom tele.itọkasi awon gomina ipinle ipinle Akwa Ibom..
wikipedia
yo
Joseph Adedúrótìmí Adetical jẹ́ ara orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti gómìnà ìpínlẹ̀ Akwa Ibom tẹ́lẹ̀.Ìtọ́kasí ̀ko ̀ko Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom..
wikipedia
yo
Daniel Nodbód jẹ́ ọmọ ológun níbi iṣẹ́ ológun ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Nígbà ìjọba ológun Ọ̀gágun Muhammadu Buhari ó jẹ́ yí ìpàmọ̀ gẹ́gẹ́ bí Gómìnà ìpínlẹ̀ Cross River lati 1984 de 1986.lórúkọJóòbù..
wikipedia
yo
Gregory Apeẹni jẹ́ ọmọ ológun ilẹ̀ Nigeria tó tifẹ̀yìntì tí ó di olùmójútó ológun fún Ìpínlẹ̀ adáwàwá àti Ìpínlẹ̀ Cross River lãrín December 1993 àti August 1996 nígbà ìjọba ológun Ọ̀gágun Sani Abacha.Ìtọ́kasí àwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ Adama Gómìnà Ìpínlẹ̀ Cross River..
wikipedia
yo
Jazz je iru orin to bere ni Amerika larin awujo awon omo Afrika Amerika.itọkasi..
wikipedia
yo
Orin Blu jẹ́ irú orin tó bẹ̀rẹ̀ ní Amẹ́ríkà gbéṣe àwùjọ àwọn ọmọ Afrika Amejìkasí..
wikipedia
yo
Iṣu (dìósa) jẹ́ ọ̀gbìn gbòngbò onítááṣì tí a lè gbin nílẹ̀ olóoru, pàápàá jù lọ ní Ìwọ̀-Oòrùn Áfíríkà..
wikipedia
yo
A ma ún gbin iṣu nipa gbi gbin ori iṣu, ó ma ún tó àkókò oṣù mẹ́fà is méjìlá laarin igba ọgbin si igbà ikórè iṣu[1]a lè jẹ iṣu, ã lè fi iṣu ṣe Iyán(oúnjẹ tó gbajúmọ̀ gan nílẹ̀ YORÙbáÀwọn itọkú si àwọn ọgbinàwọn ohun ọgbin jijẹ..
wikipedia
yo
Ẹ̀gẹ́ (Manihot esculenta)itọkasi àwọn ọ̀gbìnàwọn ohun ọ̀gbìn jíjẹ..
wikipedia
yo
Àwọn obìnrinSerena Kinkin Williams (ọjọ́ September 26, 1981) jẹ́ agbá bọ́ọ̀lù Tẹnis ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà lọ́wọ́lọ́wọ́ tó wà ẹniipo Kínní lagbaye nínú ìdíje ẹnìkan àti ẹniipo kejì nínú ìdíje ẹniméjì pẹ̀lú ẹ̀gbọ́n rẹ̀ Venus Williams(12/8/10)..
wikipedia
yo
Ijoṣe tẹnis awọn obinrin (WTA) ti fisípò kini lagbaye ni igba otooto marun..
wikipedia
yo
O tun ipo kinni gba fun igba karun ni ọjọ 2 Oṣu kọkanla 2009..
wikipedia
yo
O kọ́kọ́ bọ́ sí ipò kinni lágbáyé ní ọjọ́ 8 oṣù kẹjọ 2002..
wikipedia
yo
Ni ọjọ 3 Oṣu Keje 2010, o di eni kẹfa lori Akojọ awọn oludijeakọkọ olokikijulọ gbogbo igba lailai.Williams ni oludijeakoko lọwọlọwọ ni idije ẹnìkan ati ẹníméjì awọn obinrin ni Open Australia, oludijeakọkọ lọwọlọwọ idije enikan ni Wimbledon, ati ni idije Ẹniméjì awon obinrin ni Open Faranse ati ni Open Amẹrika..
wikipedia
yo
Ohun ni Agbayo laipẹ yi, obinrin abi ọkunrin, to gba gbogbo awọn ifẹ-eye Grand Islam mẹrẹẹrin lẹẹkanna, ati obinrin ikarun lailai to ṣe bẹ..
wikipedia
yo
Awọn ifẹ-eye Grand SIslam 17 rẹ ni ìkẹfà lori Akojọ gbogbo igba lailai..
wikipedia
yo
Williams jẹ́ ìkẹrin bíi àwọn Ifẹ̀-ẹ̀yẹ Grand SIslam Àwọn Obìnrin tó gba n'igba Open, lẹ́yìn Steffi Graf (Ife-ẹ̀yẹ 22) àti Chris Evert àti Martina NavbáàOlórí (Ife-ẹ̀yẹ 18)..
wikipedia
yo
O ti gba awọn ifẹ-eye Grand Sale ni idije enikan, awon obinrin ẹníméjì ati àdàpọ̀ ẹní ju obinrin agbayo miran lo lọwọlọwọ.Williams ti gba eso wura látinú ikan ninu idije awon obìnrn enikan ati meta ninu idije awon obinrin ẹníméjì pelu egbon rẹ̀ Venus Williams..
wikipedia
yo
Williams ti gba ẹbun owo fun iṣẹ ju obinrin elere-idaraya miran lọ lailai..
wikipedia
yo
Williams ni àbúrò Venus Williams tó ti wà ní ipò kinni lagbaye tẹ́lẹ̀..
wikipedia
yo
Wọ́n ti bá ara wọn gbayó nígbà 23 ìdíje alágbàṣe láti 1998, Serena borí ni 17 àwọn ìdíje wọnyi títí di oṣù kẹwa 2013..
wikipedia
yo
Títí di oṣù keje 2009, wọ́n ti pàdé ní òpin ìdíje Grand Rale mẹjọ, Serena borí ní emẹfa..
wikipedia
yo
larin open Faranse 2002 ati Open Australia 2003, won pade ni opin awon idije enikan gbogbo Grand Sale mẹ́rẹ̀rin, igba akoko ni igba Open ti awon oludije meji kanna dije fun opin Grand Sale ni títẹ̀léntẹ̀lé..
wikipedia
yo
Àwọn méjèjì ti gba ìfẹ́-ẹ̀yẹ Grand Sale 12 Ìdíje ẹníméjì bí Ìdár.Ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésíayéWilliams jẹ́ bíbí ni Saigi, Michigan fún Richard Williams àti Ọ̀rácene Price..
wikipedia
yo
Nígbà tí àwọn ọmọ ṣì kéré, ẹbí wọn kó lọ sí àdúgbò ìtòsí Los Angeles Compton, níbi tí Serena ti bẹ̀rẹ̀ síní gbà tẹnis nígbà tó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́rin..
wikipedia
yo
Toríẹ ló ṣe jẹ́ pé dòní àwọn òbí rẹ̀ ni wọ́n kò ní tẹnis gbígbà.Ẹ̀bi Williams kó lọ sí West palm Beach ní Florida láti Compton nígbà tó jẹ́ ọmọ ọdún mẹsan kò le bà lé lọ sí Adèmí Keniola ti Rick Macci, tó fu ní ẹ̀kọ́ Eré-ìdárayan yìókù..
wikipedia
yo
Bó tilẹ̀ jẹ́ pé nígbà míràn kò fẹnukò mọ́ baba Williams ó ìtẹríba fún pé "Ó tọ́jú àwọn ọmọbìnrin rẹ̀ bí ọmọdé, ó sì gbà wọ́n láàyè láti wúwá bí ọmọdé”
wikipedia
yo
Richard dáwọ́ rírán àwọn ọmọ rẹ̀ lọ sí àwọn ìdíje ọmọdé nígbà tí Williams jẹ́ ọmọ ọdún 10, nítorípé ó jẹ́ kí wọ́n ó ṣe èrò láti kọjú sí ẹ̀kọ́ wọn..
wikipedia
yo
Idì miran tún ni nítorí ẹ̀yà, ó gbọ́ pé àwọn obí àgbàyó aláwọ̀funfun únsọ̀rọ̀ burúkú nípa àwọn Arabinrin Williams nígbà ìdíje..
wikipedia
yo
Nígbà yí, Williams ní Record 46-3 lórí ìrìnkiri ìdíje àwọn ọ̀dọ́ ti ìjọṣe tẹnis orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà, ohùn ló sì jẹ́ ẹni àkọ́kọ́ lãrín àwọn àgbàyọ̀ tọmọ ọdún wọ́n kọjú 10 lọ ní Florida..
wikipedia
yo
Ní 1995, Richard mú àwọn ọmọ rẹ̀ kúrò ní ààdèmí Macci, Látìgbà na lo ohun ló ti únṣe ẹ̀kọ́ eré-ìdárayá fún wọn..
wikipedia
yo
Nígbà tí wọ́n bẹ̀rẹ̀ lọ́wọ́ rẹ̀ ní 2000 bóyá nípa títẹ̀lé ọ̀nà tí àwọn yìókù gbà nípa yọyọ nigbogbo ìgbà ní àwọn ìbòpọ̀ òdò kò bá fún ní anfani, Williams dahun pé "oníkálùkù únṣe ohun ọ̀tọ̀..
wikipedia
yo
O pòfo ayọ̀ akọkọ si ẹniipò 149 lagbaye, Annie Miller lãrín wákàtí kan ayọ̀ ó sì gba US$240 bí ẹ̀bùn owó.Williams kò gba ayọ̀ kankan ní 1996..
wikipedia
yo
Ni 1997 o pòfo ni ayo tọ́ka mẹta ni ìdíje mẹta ko tọ dipé o bori ninu ayo akọkọ rẹ ni Oṣu kọkanla ni Ameritech Cup Chicago..
wikipedia
yo
Niida bi ẹniipo 304 lagbaye, o bori eni 7 Mary Pierce ati eniipo 4 Monica ṣẹlẹs, eyi fun ni ibori rẹ akọkọ lori awọn agbayo onípò mẹwa akọkọ, o si di agbayo onípò to kerejulọ ni igba Open to bori awọn olodi ni ipo mẹwa akọkọ ninu idije kan..
wikipedia
yo
Nígbẹ̀yìn ó pòfo ni ìkejìòpin sí ẹniipò 5 lágbàyé Lindsay Davenport..
wikipedia
yo
Williams began 1998 at the Medibank International Sydney..
wikipedia
yo
As a qualifier ranked World No. 96, she defeated World No. 3 Davenport in the quarterlátọwọ́ before losing to àràntxa Sánchez viclòyára in the ṣẹ̀mífinals..
wikipedia
yo
Williams made her debut in the main draw of a grand , tournament at the Australian Open, where she defeated sixth seèdèd ìrìnà SpirLea in the first round before losing to sister Venus in the second round, in the sisters' first professional match..
wikipedia
yo
Williams reached six other quarterẸ̀jẹ̀ during the year but lost all of them, including her first match against World No..
wikipedia
yo
1 Martina HinGis at the Lipton international dọ́làrs Championships in key BiscaÈÈYÀN and her second match against Venus at the Italian open in Rome..
wikipedia
yo
She treaty to reach the quarterjí of any Grand , tournament the remainder of the year, losing in the fourth round of the French open to Sánchez vicdénúdénú and the Third round of both Wimble and the us open, to Virginia ruano pascual and SpirLea, aláṣẹctivelyly
wikipedia
yo
She did, however, win the mixed Doubles titles at Wibledon and the us open with Max Mirnyi, Compleleting the Williams family's sweep of the 1998 Mimọla Doubles Grand Rlin Tour)".
wikipedia
yo
Williams won her first professional title in Doubles in Oklahoma city with Venus, becoming the third pair of sisters to win a WTA title..
wikipedia
yo
The Williams sisters wọn two more Doubles titles together during the year..
wikipedia
yo
Venus Ebony starr Williams (ọjọ́ìbí 17 Oṣù Kẹfà, 1980) jẹ́ ará Amẹ́ríkà àgbà Tẹnis alágbàṣe tó wà ní ipò karùn lagbaye fún àwọn adije ẹnìkan àti ipò Kínní lágbàyé fú àwọn adije ẹníméjì..
wikipedia
yo
Ó ti wà ní ipò kinni lágbáyé fún àwọn adije ẹnìkan látọwọ́ WTA ní ẹ̀mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀..
wikipedia
yo
Ó bọ́ sí ipò àkọ́kọ́ lágbàyé ní ìgbà àkọ́kọ́ ní ọjọ́ 25 oṣù kejì, 2002..
wikipedia
yo
Venus ni egbon Serena Williams to un na je agba oles.Ìtọ́kasí ara Ameriìyọnuwon omo Afrika Amerisee agba ti Ara Améka Meobaka a idije Wimbledon a Kuti To Kaomo to gba eso Wúrà látinú orile-ede Amerika..
wikipedia
yo
Rafael Francisco AlBurteri de Castro (ọjọ́ 14 June 1940, ni Santo Domingo) ní igbákejì Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Dominiki Olómìnira, lábẹ́ Ààrẹ Leonel Fernandez, láti August 2004 tó sì jẹ́ titundibo ní May 2008..
wikipedia
yo
Ó búra sí iṣẹ́ ní 16 August 2008.Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1940àwọn ara Dominiki Olómìnira..
wikipedia
yo
Òṣèlú aṣojú is a variety of Democracy founded on the principle of elected People representing a group of people, as opposed to Direct Democracy..
wikipedia
yo
For example, two countries which use Representative Democracy are the United Kingdom (a Constitutional monarchy) and Germany (a federal Republic).It is an element of both the parpersonary system and Presidential system of government and is typically used in a lower Chamber such as the house of commons (UK) or bundestag (Germany), and is How curyẹín by Constitutional ConstraJackson such as an upper Chamber..
wikipedia
yo
It has been described by some political thethatts as polYarchy.itọkasi..
wikipedia
yo
This page contains a list of presidents of the Dominican Republic..
wikipedia
yo
Ẹ̀yà àwọn ènìyàn dúdú jẹ́ ọkQn ìpínsísọ̀rí àwọn ẹ̀yà lágbàáyé, látàrí ìrísí àwọ̀ àti ìrísí wọn..
wikipedia
yo
Àmọ́ ṣá, kìí ṣe.Gbogbo ẹni tí àbá pé ní aláwọ̀ dúdú náà ni wọ́n du láwọ̀, bí kò ṣe wípé wá fi má ń ṣàdáyanrí irúfẹ́ ẹ̀yà tí ẹnìkan tàbí ẹlòmíràn jẹ ni..
wikipedia
yo
Ní ìlú àwọn aláwọ̀ funfun, wọ́n ma ń tọ́ka sí ẹni tí kò bá fín lawọ́ bíi tiwọn gẹ́gẹ́ bí eniyan dúdú..
wikipedia
yo
Wọ́n sábà ma ń lo gbólóhùn “dúdú” fún àwọn ènìyàn tí wọ́n wá láti sub-Saharan Africa àti àwọn ènìyàn tí wọ́n bá ti wá láti Oceania..
wikipedia
yo