cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Aliyu Modibbo Umar (15 November, 1958) jẹ oloselu ọmọ ile Naijiria to di alakoso eto agbara ati irinlile labẹ ijọba Aare Olusegun Obasanjo ni 23 May, 2003; alakoso eto Oro-aje ni July 2006 titi de July 2007 ati alakoso agbegbe oluilu apapo ile Naijiria titi de October 2008.Ìtọ́kasí ara Naijiria..
wikipedia
yo
lIyel Imọke jẹ oloselu ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà ati gomina ìpínlẹ̀ Cross River lati 2007.Ìtọ́kasí Gomina Ipinle Cross River..
wikipedia
yo
Emmanuel Eweta Uduakhan (Ọjọ́ìbí 22 October 1954) ní Gómìnà Ìpínlẹ̀ Delta lọ́wọ́lọ́wọ́ ní Nigeria láti May 29 2007, ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ olóṣèlú People's Democratic Party (PDP)..
wikipedia
yo
Kí ó tó di Gómìnà ó jẹ́ Aṣàkóso fún ìlera ní ìpínlẹ̀ Delta àti akọ̀wé fún ìjọba ìpínlẹ̀ Delta.Ìtọ́kasí àwọn Gómìnà ìpínlẹ̀taawọn olósèlú ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Martin elechi je oloselu ara Naijiria ati gomina ipinle ẹbọnyí lati 2007.itọkasiàwọn oloselu ara Naijiriàwọn gomina ipinle ẹbọnyí..
wikipedia
yo
(ti won bi ni ojo kerin osu kerin odun 1952) je gbajumo oselu omo bibi ipinle Edo lorilẹ ede Naijiria..
wikipedia
yo
Oun ni Alaga ẹgbẹ oselu-ṣèjọba ti All Progressives Congress(APC)..
wikipedia
yo
Oshihole ti fìgbà kan jẹ́ gómìnà ìpínlẹ̀ Ẹdó láti ọdún 2008 sí ọdún 2016 lábẹ́ aṣiya ẹgbẹ́ òṣèlú Action Congress of Nigeria..
wikipedia
yo
Kí ó tó di àkókò yìí, òun ni alága ẹgbẹ́ àwọn òṣìṣẹ́, NLC lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà nígbà ìṣèjọba Ààrẹ Ana, Olusegun Obasanjo.Àwọn Ìtọ́kasíàwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ẹdó..
wikipedia
yo
Olusegun Oni je oloselu ara Naijiria ati gomina ipinle Ekiti tele.Awon Ọjọ́ìbí ni 1954awon Gomina ipinle Ekiti..
wikipedia
yo
Sullivan Iheanacho Chime (Ọjọ́ìbí 10 April 1959) ni Gómìnà ìpínlẹ̀ Enugu ni Nigeria lati 29 May 2007.Ìtọ́kasí Gómìnà ìpínlẹ̀ Enugu..
wikipedia
yo
Mohammed Danjuma gòjé jẹ oloselu ọmọ ile Naijiria ati gomina Ipinle Gombe lati 2003.itọkasiàwọn oloselu ara Naijiria..
wikipedia
yo
Ikedi Godson Ohakim (Ọjọ́ìbí 4 August, 1957) jẹ́ olóṣèlú ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríààti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ìpínlẹ̀ lati 2007 títí dé 2011.Ìtọ́kasí Gómìnà ìpínlẹ̀ ìmọ̀..
wikipedia
yo
Sule lamido (born 1948) jẹ oloselu ọmọ ile Naijiria..
wikipedia
yo
O jẹ gomina ipinle Jigawa ati alakoso ọrọ okere Naijiria tele.itọkasiàwọn oloselu ara Naijiriàwọn gomina ipinle Jigawa..
wikipedia
yo
Mohammed Nmádì Sambo (Ọjọ́ìbí August 2, 1954) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti igbákejì Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà tẹ́lẹ̀ fún ìjọba Ààrẹ Goodluck Jonathan..
wikipedia
yo
O tun ti jẹ Gomina Ipinle Kaduna lati 2007 titi de 2010.itọkasiàwọn Igbakeji Aare ile NaijiriLóríawọn oloselu ara Naijiriàwọn Gomina Ipinle Kaduna..
wikipedia
yo
Ibrahim Shekarau (Ọjọ́ìbí November 5, 1955) ló ti jẹ́ gómìnà ìpínlẹ̀ Kano ní Nigeria láti 29 May 2003..
wikipedia
yo
O je omo egbe oloselu Anpp.Ìtọ́kasí oloselu ara Naijiria..
wikipedia
yo
Ibrahim Shema jẹ́ olóṣèlú ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti gómìnà ìpínlẹ̀ Katn láti 2007.Ìtọ́kasí gómìnà ìpínlẹ̀ Kat..
wikipedia
yo
Adamu Aliero je oloselu omo ile Naijiria ati alakoso agbegbe oluilu apapo ile Naijiria ni Abuja lati odun 2007.Awon itọkasiàwọn oloselu ara Naijiriàwọn gomina ipinle Kebbi..
wikipedia
yo
Mahmud Shinka je oloselu omo ile Naijiria ohun si ni gomina ipinle Zamfara, tele o je omo egbe oloselu Anpp, loni omo egbe People's Democratic Party ni se..
wikipedia
yo
Ẹlẹ́sin Mùsùlùmi pẹ̀lú ìyàwó mẹta.Ìtọ́kasí àwọn Gómìnà ìpínlẹ̀ Zamfara..
wikipedia
yo
Chibuike Rotimi Amaechi,jẹ́ olóṣèlú ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti gómìnà ìpínlẹ̀ Rivers State ní ìgbà kan rí,Ó sì jẹ́ Mínísítà fún Ètò Irin Oko.Ìtọ́kasí Ọdún Ìpínlẹ̀ Rivers..
wikipedia
yo
Sai Usman naṣamu dakingari jẹ́ olóṣèlú ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kebbi láti ọdún 2007.Ni 30 June, 2007 dakingari gbé Zainab Yar'Adua tó jẹ́ ọmọ Ààrẹ Umaru Yar'ani ìyàwó. Iyawoàwọn Itọ́kasí ara olóṣèlú ará Nàìjíríà Gómìnà Kebbi Kebbi..
wikipedia
yo
Ibrahim Idris jẹ́ olóṣèlú ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti gómìnà ìpínlẹ̀ kogi láti ọdún 2003..
wikipedia
yo
O jẹ ọmọ ẹgbẹ oloselu PDP.Ìtọ́kasíàwọn oloselu ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Abubakar Bùkọ́lá Sàràkí, , (ọjọ́ ìbí rẹ̀ ní ní ọjọ́ kọkàndínlógún, oṣù kọkànlá, ọdún 1962) jẹ́ olóṣèlú kan ní ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ààrẹ kẹtàlá ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin orílẹ̀ èdè Nàìjíríà láti ọdún 2015-2019, àti pé òun náà ni Ààrẹ kẹjọ fún ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O je gomina ni Ipinle Kwara lati odun 2003 titi de 2011 labẹ awon omo egbe PDP ( People Democraposition Party) o si tun je asoju Central Senatorial District ti Ipinle Kwara ni laarin odun 2011 si 2019, o lo saa akoko labẹ abe ẹgbẹ oselu People Democratic Party ati saa keji labẹ ẹgbẹ oṣelu All Progressive Congress.Ni ojo ti o gbeyin osu keje ọdun 2018, ni Saraki kuro ni ẹgbẹ APC, ti o si pada si ẹgbẹ PDP ti o wa ni akoko, ti o fi di Aare ẹgbẹ alatako ..
wikipedia
yo
Sàràkí kéde pé òun yóò wà lára àwọn tí wọ́n sára fún ipò Ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, tí ó sì ra ìwé tí wọ́n ń pè ní Presidential ticzel ní ìdìbò ọdún 2019,àmọ́ nínú ìbò abẹ́lé, ó fi ẹ̀yìn lé lé nígbà tí Atiku Abubakar jáwé olúborí..
wikipedia
yo
Àmọ́ ó tún tẹ̀síwàjú láti kéde pé òun ni Olùdarí àgbà ẹgbẹ́ tí ó ń ṣètò ipọnlógo fún Atiku Abubakar tí ń du ipò Ààrẹ ní ìdìbò gbogbogbòò ní ọdún 2019, ṣùgbọon òun náà fẹ̀hìn lè lé nígbà tí Ààrẹ Muhammadu Buhari jáwé olúborí tí ó pàdé di Ààrẹ fún orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.Ìdílé bí Bídára ní ọjọ́ kọ́kàndínlógún oṣù Kejìlá ní ọdún 1962 ní Londonu tí ìyá rẹ̀ ń jẹ́ Florence MoreNike Sàràkí àti baba rẹ̀ Olúṣọlá Sàràkí, tí òun náà nígbà kan rí ti jẹ́ adarí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Bukola Sàràkí fẹ́ Tóyìn sàràkí (née ojora), tí wón sì jo bí ọmọ mẹrin.Eto ẹ̀kọ́sàràkí jade ní ilé ìwé ẹ̀kọ́ gíga King's College, ní Lagos, níbi tí ó ti jáde ní ọdún 1978..
wikipedia
yo
Ó kúrò níbẹ̀ ó lọ sí Cheltenham College, èyí tí ó jẹ́ ilé ìwé (boarding School) ní United Kingdom láti 1979 títí dé 1981..
wikipedia
yo
Ti o túnbọ́ tẹsiwaju lati lọ kawe si ni Fasiti ti wa ni London ni ile iwosan ti London Medical College lati ọdun 1982 ti ti di 1987 ni bi ti o ti kawe gboye Bachelor of Medicine, Bachelor of Surgery.ibẹrẹpe iṣẹ ṣiṣeSaraki ṣiṣe ni ile iwosan Rush Green ni EsSex gege ni oniwosan ni ọdun 1988 si ọdun 1989..
wikipedia
yo
Sàràkí tún jẹ́ olùdarí ilé iṣẹ́ ìfowópamọ́sí ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ti orúkọ ilé ìfowópamọ́sí náà sì ń jẹ́ Société Générale (NIG) Ltd láti ọdún 1990 sí 2000..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2000, Aare Olusegun Obasanjo fi Ṣọ́ọ̀lù jẹ oluranlowo pataki si Aare lori bi ase n nawo.itọkasiàwọn oloselu ara Naijiriàwọn Gomina ipinle Kwaraàwọn ọmọ ile alàgbà ile Naijiria..
wikipedia
yo
Aliyu doma je oloselu omo orile ede Naijiria ati gomina ipinle Nasarawa laarin odun 2007 si 2011.Ìtọ́kasíàwọn oloselu ara Naijiria..
wikipedia
yo
MÚ'WÉ Babangida Aliyu je oloselu omo ile Naijiria ati gomina ipinle Niger lati odun 2003.itọkasiawon gomina ipinle Niger..
wikipedia
yo
Gbenga Daniel je oloselu omo ile Naijiria ati gomina ipinle ogun lati odun 2003.Ìtọ́kasí Gomina Ipinle Ogun..
wikipedia
yo
Olusegun Ososo je oloselu omo ile Naijiria ati gomina ipinle Ondo lati odun 2009 de odun 2017..
wikipedia
yo
ỌJỌ́ KẸTA OṢÙ ọ̀wàwà ni wọ́n bí Olusegun Rahman Oiku ọdún 1954..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ olùdíje fún ipò ṣenétọ̀ ni agbègbè àárín fígbún Òndó lábẹ́ ẹ̀gbẹ́ òṣèlú Zenith Labour Party nínú ìdìbò tó wáyé ní ìpínlẹ̀ Òndó.Olúṣẹ́gun ni Gómìnà alágbádá Ẹlẹ́lé-ún ní ìpínlẹ̀ Òndó, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti 2009 sí ṣaaìdẹ̀ra..
wikipedia
yo
Mímikò ti fi ìgbà kan jẹ́ Mínísítà Ìjọba Àpapọ̀ fún Ilẹ̀ àti Ìdàgbàsókè Ìgbèríko, Seketí sí Ìjọba Ìpínlẹ̀ Oǹdó, bẹ́ẹ̀ náà ni ó jẹ́ gómìnà àkọ́kọ́ tí ó jẹ́ lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú Labour Party ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Bákannáà ni ó jẹ́ Komisona lẹẹmeji fún Ètò Ìlera.Ìlú Òndó ní ìpínlẹ̀ Òndó, apá ìwọ̀-oòrùn Gúsù orílẹ̀-èdè Nigeria..
wikipedia
yo
Àti kékeré ni ó ti nífẹ̀ẹ́ sí òṣèlú, èyí sì farahàn nínú àwọn ipò tí ó dì mú nígbà tí oh wà ní ilé-ìwé àwọn oníṣègùn òyìnbó ní University of ìfẹ́ (tó di Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ University lónìí)..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ìgbà tí ó parí Agùnbánirọ̀, ó bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣíṣe oníṣègùn òyìnbó..
wikipedia
yo
Ni ọdún 1985, ó dá ilé-iṣẹ́ mọ̀nà MediClinic sílẹ̀ ni Òndó èyí tí ó dúró gẹ́gẹ́ bí ohun ètò ọ̀fẹ́ fún agbègbè náà.Ìtọ́kasíàwọn Gómìnà ìpínlẹ̀ Òǹdó..
wikipedia
yo
Jonah David Jang jẹ́ ọmọ ológun titi feyinti ati oloselu ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà, ohun ni Gómìnà ìpínlẹ̀ Plateau lati ọdún 2007..
wikipedia
yo
Nígbà ìjọba ológun Ọ̀gágun Ibrahim Babangida ó di gomina àwọn ìpínlẹ̀ Benue àti Ggóngó.Awon olóṣèlú ara Naijiria..
wikipedia
yo
DÁNAT suntáì je oloselu omo ile Naijiria ati gomina ipinle Taraba lati odun 2007.itọkasiàwọn oloselu ara Naijiria..
wikipedia
yo
Mamman Bello Ali (1958 – 27 January, 2009) je oloselu omo ile Naijiria ati gomina ipinle Yobe lati odun 2007 titi de 27 January, 2009 nigba to di alaisi..
wikipedia
yo
Kí ó tó di gomina ó ti kọ́kọ́ jẹ́ alàgbà ní ilé ìwáko ilé Ìgbìmọ̀ asòfin Nàìjíríà láti 1999..
wikipedia
yo
O di aláìsí ní 27 January, 2009 nípa àìsàn Leuasetọ́kasí olóṣèlú ará Naijiri Ọjọ́ìbí ní 1958àwọn Ọjọ́aláìsí ní 2009..
wikipedia
yo
Ibrahim Gidam (ibi 15 September, 1956) jẹ oloselu ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà ati gomina Ipinle Yobe o je ara Aba buburti ni agbegbe ijoba ibile Yunusari ni Ipinle Yobe.Awon oloselu ara Naijiria..
wikipedia
yo
Siste ìwọ̀n ìwọ̀n mítà jẹ́ ìwọ̀n síste Afọwọ́ ti orílẹ̀-èdè Fránsì kọ́kọ́ gbà ṣe ní 1791 tó sì ti di síste ìwọ̀n ẹyọ tó wọ́pọ̀ tí gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè Àgbáyé ń lò.Ìtọ́kasí àwọn síste àwọn ẹyọ..
wikipedia
yo
Hífìke Lucas Pomba (ọjọ́ August 18, 1935) jẹ́ olóṣèlú ọmọ ilẹ̀ Namibia..
wikipedia
yo
Wọ́n kọ́kọ́ dìbòyàn wọlé ní 2004, ó sì tún pàdé yọrí nínú ìdìbòyán tó wáyé ní 27 àti 28 November, 2009..
wikipedia
yo
Egbe oloselu SWAPO ti Pohamba je olori gba 77.82% ibo.Ìtọ́kasí awon ara Namibia..
wikipedia
yo
Omẹ́tàhehemen Osunbor jẹ́ olóṣèlú ará ilẹ̀ Nàìjíríà ati alàgbà lati Edo ni ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lati 1999 títí dé 2007..
wikipedia
yo
Ohun sí ló tún ti jẹ́ Gómìnà ìpínlẹ̀ Ẹdó láti 2007 dé 2008.Ìtọ́kasí Gómìnà ìpínlẹ̀ Ẹdó..
wikipedia
yo
Bélùpọ́n jẹ́ abà ní ìpínlẹ̀ Oyo ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Àwọn ìlú àti abúlé ní ìpínlẹ̀ Oyo..
wikipedia
yo
Brooklyn jẹ agbegbe kan ni Ilu New York ni Amẹrika.Ìtọ́kasí awọn ilu ni orilẹ-ede Amẹrika..
wikipedia
yo
Dallas Ọpọ́n jẹ́ Ìlú tó ní Olùbùgbé jùlọ Kẹjọ ní Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà àti tó ní Olùbùgbé jùlọ Kẹta ní Ìpínlẹ̀ Texas.Ìtọ́kasí Àwọn Ìlú ní Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
David Hume (7 May 1711 [26 April O.S.] – 25 August 1776) jẹ́ amòye, akotan, onímọ̀ ọ̀rọ̀-OKÒWÒ, àti ALÁlòpọ̀ ARA SULY, TO gbajúmọ̀ fún iṣẹ́ àti iṣèrò oníyẹye rẹ̀.Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1711 Ojolọ́ko ní 1776àwọn ará Britani..
wikipedia
yo
Max Planck (April 23, 1858 – October 4, 1947) jẹ́ onímọ̀sáyẹ́ǹsì ará ilẹ̀ Germany.Ìtọ́kasíàwọn ẹlẹ́bùn Nobel ninu Fisiksiàwọn ẹlẹ́bùn Nobel ara Jemani..
wikipedia
yo
Werner Heìṣẹ̀ǹbáyéberg (5 December 1901 – 1 February 1976) jẹ́ ara Germany tó jẹ́ onímọ̀ Fisiélaz onírò tó ṣe ṣe pàtàkì sí ìṣiṣẹ́ èrò àṣeréṣeré tí ó sì gbajúmọ̀ fún titẹnumọ́ ọ̀pọ̀ àìdájú fún ìró ataṣeré..
wikipedia
yo
Bakanna, o tun se afikun pataki si Fisiksi inutọ́tọ́, iro papa ataṣere, ati Fisiksi eléruku.K]berg, pẹlu Max Born ati Paelecual Jordan, se ilalele apoti nọmba fun iṣiṣẹ ẹrọ ataṣere ni 1925..
wikipedia
yo
Heloyaberg gba ebun Nobel ninu Fisikùkùté ni 1932.leyin Ogun Àgbáyé keji, O di oludari Aṣáájúa Wilhelm Institute for Physics, to yi oruko si Max Planck Institute for Physi..
wikipedia
yo
Ohun ni oludari ile-ajo yi titi ti won fi gbe lo si Munich in 1958, nibi ti won ti fe po si, ti wo si tun yi oruko re si Max Planck Institute for Physics and sìíphysics..
wikipedia
yo
Heloyaberg je Aare German research Council, Alaga Commission for Atomic physics, Alaga Nuclear Physi working group, ati Aare Alexander von Humboldt Foundation.Ìtọ́kasí ẹlẹ́bùn Nobel ninu Fisiksiàwọn ẹlẹ́bùn Nobel ará Jemani..
wikipedia
yo
Charles John Huìpinnum Diedisitọ́kasí àwọn ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì..
wikipedia
yo
Nicolas Alejandro Massu Fried (Ọjọ́ìbí October 10, 1979, ni Viña del Mar, Chile) jẹ́ àgbà Tennis ará Chile tó ti feyinti.Ìtọ́kasí Agba Tẹniṣàwọn tó gba eso Wúrà Olimpi..
wikipedia
yo
Milwaukee jẹ́ ìlú kan ní Ìpínlẹ̀ Wisconsin ní Orílẹ̀-Èdè Amẹ́ríkà.Ìtọ́kasí Ìlú ní Orílẹ̀-Èdè Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Frankfurt am main je ilu ni Jemani.itọkasi awon ilu ati Abule ni Jemani..
wikipedia
yo
Àwọn Erékùṣù Solomoni (Solomon Islands)Ìtọ́kasí Solomoni..
wikipedia
yo
Ìwé jẹ́ àkójọpọ̀ tàbí àkọ́papọ̀ àwọn ohun tí a kọ, tẹ̀, yasawòrán, tàbí àwọn ojú-ìwé ọlọ́fọ̀ tí a ṣe láti inú àwé-Ìwé tàbí èròjà miraníto..
wikipedia
yo
Alfred Bernhard Nobel(Stockholm, Sweden, 21 October 1833 - SanRemo, Italy, 10 December 1896) jẹ́ onímọ̀iṣẹ́-ẹ̀rọ omo ilẹ̀ Sweden.Ìtọ́kasí Àwọn Ọjọ́ìbí ní 1833àwọn ojoaláìsí ní 1896awon ara Swídìn..
wikipedia
yo
Wellington ni oluilu orile-ede New Zealand.itọkasi..
wikipedia
yo
Toronto ni Ilu tótóbitó ni orilẹ-ede Kánádà.itọkasi àwọn ìlú ati abúlé ni Kánádà..
wikipedia
yo
Ilu Mekṣíkọ̀ ni oluilu orile-ede Mexico.Ìtọ́kasí Mekṣíkọ̀..
wikipedia
yo
Kingston ni oluilu àti ìlú tótóbitó ní Jàmáíkà.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn olúìlú ní Ariwa Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Olùfẹ́ Olufemi Anikulapo Kuti (ọjọ́ìbí 16 June 1962) je olorin omo orile-ede Naijiria.gbajugbaja akorin yi ni a mo si Femi Kuti..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ akọrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí a bí ní ìlú Londontí ó dàgbà sí ìlú Èkó..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ àkọ́bí ọmọ okùnrin ọmọ bíbí olùdásílẹ̀ orin afrobeat tí a mọ̀ sí Fela Kuti àti ọmọ ọmọ akíkanjú olóṣèlú, ajà fún ètò àwọn obìnrin, ìyá ààfin Olufunmilayo Ransome-Kuti.Àwọn Ìtọ́kasíàwọn Ọjọ́ìbí ní 1962àwọn ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Sultanu ilu Sokoto tabi Sultani ilu Sokoto ni oruko oyè Kálì ilu Sokoto, ohun na lo si tun je baba agba fun awon Musulumi ni àparirù Naijiria.Sulran ori oye lowolow ni Muhammed sa'adu Abubakar.sultanu ilu Sokoto Sokoto..
wikipedia
yo
Aláàfin tàbí Aláàfin ìlú Ọ̀yọ́ jẹ́ orúkọ oyè ọba ìlú Ọ̀yọ́..
wikipedia
yo
Agbègbè tí wọ́n ti ń ṣèjọba wà ní apá ìwọ̀ oòrùn ilẹ̀ Afrika..
wikipedia
yo
Láti ọdún 1900 tí wọ́n ti apá ìwọ̀-oòrùn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà gẹ́gẹ́ bíi kókóìlú, gbogbo olórí ìlú náà ti jẹ́ yálà Òyìnbó aláwọ̀ funfun tàbí ọmọ dúdú tó gbajúmọ̀ gan-an.Nínú Èdè Yorùbá, wúnrẹ̀n "Ọba" túnmọ̀ sí olórí ìlú..
wikipedia
yo
Gbogbo ìlú tó wà ní ilẹ̀ Yorùbá ló ni orúkọ tí wọ́n ń pe Ọba wọn..
wikipedia
yo
Ní ìlú Ọ̀yọ́, Aláàfin ni orúkọ tí wọ́n n pe ọba wọn, èyí tí a lè túnmọ̀ sí "Ẹni tó ni àfin".Orúkọ àwọn Aláàfin tó ti jẹ́ sẹ́yìntún wọ WorldStatesmen Nigeria- Traditional stateṣàwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
AbDelaZ Boutefabókùúsọ̀rọ̀ (; ) (Ọjọ́ìbí March 2, 1937) jẹ́ olóṣèlú àti Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Algeria lati ọdún 1999.Ìtọ́kasí ara Algeria..
wikipedia
yo
Ahmed oúYahia () (Ọjọ́ìbí July 2, 1952) jẹ́ olóṣèlú ọmọ ilẹ̀ Algeria, ohun sì ni Alakoso agba ile Algeria lati Oṣù Kẹfà 2008 Wá Ka.Ìtọ́kasí ara Algeria..
wikipedia
yo
José Eduardo dos Santos (Ọjọ́ìbí August 28, 1942) ni Ààrẹ ilẹ̀ Angola lọ́wọ́lọ́wọ́, ó bọ́ sí orí àga ní ọdún1979 until 2017..
wikipedia
yo
Ohun na tun ni Aare egbe oloselu popular Movement for the Liberation of Angola (MPLA). Àwọn Aare ilẹ̀ Angola..
wikipedia
yo
Samuel Johnson (24 June 1846 – 29 April 1901) jẹ́ àlùfã Ìjọ Anglikáni ọmọ Yorùbá tí ó kọ ìtàn Yorùbá pẹ̀lú àkọlé A History of the Yorùbás From The Earliest Times to the Begin of the British Proán tí wọ́n tẹ̀jáde ní ọdún 1921 lẹ́yìn ikú rẹ̀.Ìtọ́kasí Ọjọ́ìbí ní 1846àwọn Ọjọ́-aláìsí ní 1901àwọn ọmọ Yorùbá..
wikipedia
yo
Samuel Johnson (18 September ránsi 13 December 1784)Àwọn ìtọ́kasí àwọn ara Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì..
wikipedia
yo
Festus Gonçtebanta gawa (Ọjọ́ìbí 21 August 1939) lo je Aare orile-ede Botswana lati 1998 titi de 2008.Ìtọ́kasí awon ara bots Aare ile Botswana..
wikipedia
yo
Gobatse Khama Ian Khama tàbí Ian a seretse {òjò 27 February 1953) ni Ààrẹ orílẹ̀-èdè Botswana láti ọjọ́ kinni oṣù kẹrin ọdún 2008..
wikipedia
yo
Ni Oṣu Kẹrin ọdun 2022, Ìdájọ́ ti Orilẹ-ede rẹ pe Ian Khama..
wikipedia
yo